Proverbs stringlengths 8 373 | Labels int64 0 1 |
|---|---|
Aṣọ yẹn kò ní àbàwọ́ kankan lára. | 0 |
Àwọn ilé-iṣẹ́ kan lé ọ̀pọ̀ òṣìṣẹ́ kúrò nítorí wọn kò lè san owó. | 0 |
Àgùdà ò jẹ lábẹ̀-ẹ Gẹ̀ẹ́sì. | 1 |
Olórin tí àwọn agbófinró fi sí àtìmọ́lé ti jáde ní àtìmọ́lé ọlọ́pàá. | 0 |
Ìwà àwọn ọba alayé lè mú ewu ńlá bá orí ìtẹ́ tí wọ́n jókòó lé. | 0 |
Aláșọ kan tó ní k'ọnà máa wọ, bí așọ kan náà bá gbó, ojú rẹ yóò wále. | 1 |
Gege se gegę, onígege tó lọ fásòpá; b'ọkọ bá fọwọ pa ọrún;aya á fowo pabe. | 1 |
Asòtítọ́ ò gbé ilẹ̀ Ẹ̀yọ̀; purọ́purọ́ ò gbé ilẹ̀ Awúsá. | 1 |
B'á a fún wèrè l'ọkọ, ọdọ ara rẹ ni yoo r'oko sí. | 1 |
Bí a bá jẹ̀wọ́ tán ẹ̀rín là ń rín; bí a bá yó tán orun ní ń kunni. | 1 |
Bí eégún ò bá mọ Òdèré, tí kò mọ́ Àṣàkẹ́, atọ́kùn-ún rẹ̀ ní ń wi. | 1 |
Aṣọ títà ni iṣẹ́ ìya Bùkọ́lá. | 0 |
Adìẹ-ilé l'Orúnmilà ń gbá yẹkẹtẹ (hanlẹ, pakuuru) mo. | 1 |
A kì í bá 'Mo bẹ e' bínú. | 1 |
Ìkọlù tó wáyé láàrọ̀ yìí jẹ́ èyí tó ya gbogbo wa lẹ́nu. | 0 |
Wọ́n ti kó gbogbo àwọn nǹkan náà lọ fún ìwádìí ìjìnlẹ̀. | 0 |
Aboyún kì í gbọn kílẹ má jẹ lára ẹ. | 1 |
Àwòrán tó ṣàfihàn àwọn ilé tí ó jóná lọ́jọ́ náà máa jáde lọ́la. | 0 |
Àwọn èèyàn bẹ́ẹ̀ ń lọ sókè òkun lọ parọ́ ohun tí kò ṣẹlẹ̀ lọ́hùn-ún. | 0 |
Biyà 'ò kárí, enìkan, kì í kọ o. | 1 |
Aláṣejù baba àṣetẹ́. | 0 |
Ara àṣà ìranraẹnilọ́wọ́ ni ọ̀wẹ̀ bíbẹ̀. | 0 |
Fákẹ́yẹ sọ pé ọmọbìnrin náà bẹ òun pé kí òun dáwọ́ dúró lọ́jọ́ náà. | 0 |
Ìjà èmí-jù-ọ́-ìwọ-ò-jù-mí ni ní ìlú Káraóle. | 0 |
Díedíe l'Olówó ń jó. | 1 |
Àwọn èèyàn kò gbọ́ ìwàáṣù mi délẹ̀ kí wọn tó bú mi. | 0 |
Àyìndé béèrè lọ́wọ́ Adéjọbí pé ṣé ìyá rẹ̀ àgbà kò mú Làbákẹ́ lọ sí Ayédé. | 0 |
Aṣọ tí Yínká ran dúró rege sími lọ́rùn mi. | 0 |
Ó tó wákàtí mẹ́ta lẹ́yìn tí ọmọ náà kó sí kọ̀ǹga ọ̀hún kí wọ́n tó rí i yọ. | 0 |
Bí a bá ń relé ení tó gbọn juni lọ, a kì í sọrọ tó gùn, torí nínú ọrọeni ni yóó fi múni so bí eran. | 1 |
Ààrẹ Táíyélolú ló jáwé olúborí. | 0 |
Ọmọ tó kó sí kọ̀ǹga ọ̀hún ń ṣe eré pẹ̀lú ọ̀gba rẹ̀ kan kí ó tó kó sí kọ̀ǹga ọ̀hún. | 0 |
Amòní; a 'ò șài mọla, bọtùn-únla ọmọ ìyá wọn ó sunàn, enìkan ò mọ. | 1 |
Èèyàn-án rìn, òjìjí tẹ̀ lé e; kò ṣé-é mú, kò ṣé-é jù sápò. | 1 |
Babaaláwo kì í bèrè ẹbọ àná. | 1 |
Orúkọ àwọn agbésùmọ̀mí tó kọlu ìlú Ọ̀wọ̀ àti àwọn onígbọ̀wọ́ wọn | 0 |
Ààrẹ ìlú Òmìnira pàṣẹ títi àwọn arúfin mọ́lé. | 0 |
Arọ tí ń bú ogun, orí ẹlẹ́sẹ̀ méjì ló bú u lé. | 1 |
Ọ̀rẹ́ Oròbíyìí ló sọ ọ̀rọ̀ yìí di mímọ̀ fún ayé gbọ́. | 0 |
Afurasí sọ pé òun kò mọ̀ pé ọmọ kékeré lòun ń bá lò pọ̀. | 0 |
Àṣírí ìkokò, ajá kọ́ ni yó tùú u. | 1 |
Tinúbú fòǹtẹ̀ lu líla ọ̀nà tuntun láti Ìsẹ́yìn sí Òkèhò lọ Ìgànná lỌ́yọ̀ọ́. | 0 |
Afúnijẹ kì í fúni tà. | 1 |
Bọ̀dé ní òun ti di atúnbí àti ajíhìnrere. | 0 |
Àyìnlá Ọmọwúrà ṣe àwo orin tí ó tó méjìlélógún kó tó papòdà. | 0 |
A kì í fi oníjà sílẹ̀ ká gbájúmọ̀ alápẹpẹ. | 1 |
Ìró àti eruku ìbọn gba gbogbo inú ọjà náà kan. | 0 |
Ilé ìfowópamọ́ Onírèké jèrè púpọ̀ ní sáà tó lọ. | 0 |
Bàbá Bọ́lá ṣàlàyé bó ti gbé e lọ sílé ọ̀gá ọlọ́pàá Ògùn. | 0 |
Ó ní kò sí òótọ́ kankan tó jọ pé Balogun fi ṣọ́ọ̀tì pa aṣọ ojúlé kankan. | 0 |
Àwọn afurasí òṣèlú ni wọ́n ń tú àṣírí ìwà ọ̀daràn tí ìjọba ń hù. | 0 |
Ó ti lé lọ́sẹ̀ mẹ́ta tí Bọ́lá ti tẹkọ̀ létí lọ sílùú òyìnbó. | 0 |
A kì í fi gọgọ sílẹ fún Ọdáwé; a kì í fọkọọ lẹ f'Ọ́nílara | 1 |
Àbàtì àlàpà: a bà á tì, a bá a rẹ́ . | 1 |
Egberún seetí aso-ise nì. | 1 |
A kì í wà nínú ìṣẹ́ ká perin tọrẹ. | 1 |
Àáyá ò gọ̀ bíi ká fà á nírù. | 1 |
Eléyín rírà ń sòfin erín,aláso-píponń sòfin òde. | 1 |
Bí wọn ò jáwé efinrin kì í rùn. | 1 |
Bísóyè jàjàbọ́ lọ́wọ́ àwọn ajínigbé. | 0 |
Bí ọmọdé kọ iyán àná, ìtàn la ó pa fún un. | 1 |
Òjó ni orúkọ ọkùnrin tó ń gbin igbó. | 0 |
A gbọ́ pé ẹjọ́ ọmọdé jàre ná; ó ku ẹni ti yó bàá a wí i. | 1 |
B'ẹni 'ò bá șìsę, ẹni kì í là. | 1 |
Ìgbésẹ̀ tí ìjọba Èkó gbé ti ń fa awuyewuye láàárín àwọn ènìyàn. | 0 |
Ìjọba buwọ́lu ríra ohun èlò tí yóò mú kí ayélujára jáfáfá sí i ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. | 0 |
B'íbàdàn bá lẹ, àlẹgbọn nì, kì í șàlęgọ. | 1 |
Kì í ṣe ìgbà àkọ́kọ́ rèé tí wọn yóò lo ẹ̀yà kan lára ẹlẹ́dẹ̀ fi rọ́pò ti èèyàn. | 0 |
Àwọn oníròyìn fìdí rẹ̀ múlẹ̀ bí àrùn ṣe tànkálẹ̀. | 0 |
A kì í mọ̀ọ́ wẹ̀ ká káyéjá; bọ̀rọ̀kìnní kan ò wà á já; báa ṣoore títí á kù síbìkan. | 1 |
Bí i ẹgbẹ̀rún mẹ́wàá àwọn ènìyàn ló ti fi ibùgbé wọn sílẹ̀. | 0 |
Abiọdun Omotoye ni orúkọ awakọ̀ tó di olóògbé lánàá. | 0 |
Afohunpamọ ló ń sàmìì ọnà. | 1 |
Àwọn ikọ̀ ń ṣiṣẹ́ pẹ̀lú àwọn ọlọ́pàá tó wà fún ààbò àwọn ara ìlú. | 0 |
Àgbákò sọ pé ìyẹn lè gba àkókò púpọ̀. | 0 |
Àwọn Ọba dà bí òòṣà tí a ò lè fọwọ́ rọ́ sẹ́yìn láwùjọ Yorùbá. | 0 |
Àrùn tí ńṣe ogójì ní ńṣe ọ̀ọ́dúnrún; ohun tí ńṣe Abọ́yadé gbogbo ọlỌ́ya ní ńṣe. | 1 |
Ẹ ṣọ́ra fún gbígba ayédèrú ìwé ẹ̀rí àyẹ̀wò Kòrónà. | 0 |
Dùnùndún, kì í ș'onjẹ Ọlọjà. | 1 |
Ìgbésẹ̀ burúkú gbáà ni Ìdòwú tó pokùnso ní Màgbòrò gbé. | 0 |
Wọ́n ti fi fídíò oníṣẹ̀ẹ́jú méjì kan sí orí afẹ́fẹ́. | 0 |
Àrùn là ń wo; a kì í wokú. | 1 |
Ẹni ọdún mẹ́rìnlélógún ni ọ̀dọ́bìnrin yìí. | 0 |
Gbèsè'òtán lọrùn bọrọkìnní, bó kànràn kí gbèsè ó tán, a á tún je òmíràn sí i. | 1 |
Ẹni tó n duyè (du oyè) eégún ẹ kì í pẹ lóde. | 1 |
Àìtó ehín-ín ká ni à ń fọwọ́ bò ó. | 1 |
A kì í wẹ àwúre leyìn-in gbèsè. | 1 |
Ará ilé ẹni ò ṣeun; èèyàn ẹni ò sunwọ̀n; a ò lè fi wé àlejò lásán. | 1 |
Abere bo lowọ adẹtẹ ó dète, ọrọ balẹ ó dèrò. | 1 |
Èèyàn tí ò leni lẹyìn, wọn á lé e léré (laré) | 1 |
Èèyàn kì í dá jú ìpọrí e. | 1 |
Àjà-gbayìni tàrá. | 1 |
Ohun tí ìròyìn sọ ni pé ilé iṣẹ́ ìrẹsì ti ń pọ̀jù ní ìlú Èkó | 0 |
Àwọn tó fara pa yánnayànna nínú àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ń gbàtọ́jú nílé ìwòsàn ìjọba. | 0 |
Ètò ọrọ̀-ajé orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà ti rí àwọn ìpèníjà tuntun | 0 |
Àgbàlagbà tó rerù; tó tún n te pá ti fi àáro re seré (tàfalà)m | 1 |
Abíọ́dun jẹ gómìnà Èkó fún ọdún mẹ́jọ. | 0 |
Buhari ti yan ẹni tó máa gbapò lọ́wọ́ ẹ̀ bó bá kúrò lórí oyè. | 0 |
Arábámbi lóun yoo gbà èsì ìbò tí kò bá sì ìdàrú-dàpọ̀ kankan. | 0 |
B'órí 'ò sunàn, ọgbọn-inú ni kò tó. | 1 |
Subsets and Splits
No community queries yet
The top public SQL queries from the community will appear here once available.