{"id": "10020#0", "text": "Odun wo ni wọn ṣe idije Olympiiki akọkọ?"} {"id": "10118#0", "text": "Orile ede wo ni Washington DC wà?"} {"id": "11164#0", "text": "Ipa wo ni Benito Mussolini se ni Ogun World War 2?"} {"id": "11194#0", "text": "ẹgbẹ wo ni Huey Newton da silẹ?"} {"id": "11419#0", "text": "Ilu wo lo tobi ju lọ ni orile-ede Poland"} {"id": "11673#0", "text": "Ki ni oluiilu orile ede Japan?"} {"id": "12167#0", "text": "ọdún wo ẹlẹsẹ ti a mọ sí Dick Tiger ṣ'aláìsí?"} {"id": "12299#0", "text": "ilu wo lo tobi julọ ni orile-ede Mauritania?"} {"id": "13308#0", "text": "kí ni olú ìlú orile ede Puerto Rico?"} {"id": "13935#0", "text": "Awon orile ede wo ni won pe ni Balkani?"} {"id": "15096#0", "text": "Odun wo ni Andy Ruiz ati Anthony Joshua ja?"} {"id": "15124#0", "text": "ọmo orile ede wo ni John Locke?"} {"id": "15131#0", "text": "ọjọ meloo lo wa ninu oṣu february?"} {"id": "15329#0", "text": "Ọdún wo ni Namadi Sambo jẹ Gomina ipinle Kaduna ?"} {"id": "15512#0", "text": "Awon orile ede wo lo yika Austria?"} {"id": "16114#0", "text": "oṣù wo ni keresimesi má ń bọ́ sí?"} {"id": "16348#0", "text": "Egbe oloselu wo ni Boris Johnson wa pẹlu?"} {"id": "16384#0", "text": "ọdún wo ni Emomali Rahmon di ààrẹ Orile ede Tajikistan?"} {"id": "17311#0", "text": "ipinlẹ wo ni Isiala Ngwa wa ni Nàìjíríà?"} {"id": "17552#0", "text": "Ipinle wo ni ilu Orlu wa?"} {"id": "18031#0", "text": "Odun wo ni won da egbe World Health Organization silẹ?"} {"id": "18270#0", "text": "Orile ede wo ni San Marino wa?"} {"id": "19496#0", "text": "Ta ni Aarẹ orile ede Ivory Coast?"} {"id": "20231#0", "text": "Odun wo ni Augusto Pinochet je aare orile-ede Chile?"} {"id": "20613#0", "text": "Odun wo ni Jolly nyame je gomina ipinle taraba?"} {"id": "20775#0", "text": "kí ni oluilu orile-ede griisi?"} {"id": "20961#0", "text": "Omo orile-ede wo ni osere Yvonne Nelson?"} {"id": "22786#0", "text": "Ọdún wo ni Pope John Paul s'alaisi?"} {"id": "23435#0", "text": "ọdun wo ni Julius Caesar ku?"} {"id": "23534#0", "text": "Odun wo ni King Leopold ṣ'alaisi?"} {"id": "23620#0", "text": "Ki ni oruko ṣọọsi Paul Adefarasin?"} {"id": "23625#0", "text": "Ki ni olu-ilu orile-ede Egypt?"} {"id": "24640#0", "text": "ọdun wo ni Pope John Paul ṣ'alaisi?"} {"id": "24860#0", "text": "Oṣù wo ni ọdún 1967 ni ogun Biafra bẹrẹ?"} {"id": "24913#0", "text": "Odun wo ni wọn da ẹgbẹ United Nations silẹ?"} {"id": "25355#0", "text": "Orukọ wo ni a n pe orile-ede Botswana ki wọn to yi pada?"} {"id": "2596#0", "text": "Ki ni oluilu orile ede Albania?"} {"id": "26086#0", "text": "Kí ni oluilu orile-ede Finland?"} {"id": "27070#0", "text": "Odun wo ni won bi Otto von bismarck?"} {"id": "27745#0", "text": "ọmọ orile ede wo ni Samuel Peters?"} {"id": "28208#0", "text": "ọdún wo ni wọn kọkọ bẹrẹ ẹbun Nobel ?"} {"id": "3017#0", "text": "Nibo ni Naijira ni Nok wa?"} {"id": "30269#0", "text": "ọdún wo ni alpha conde jẹ ààrẹ Orile ede guinea?"} {"id": "31034#0", "text": "Iwe meloo ni Mary Anne Evans kọ?"} {"id": "31099#0", "text": "Odun wo ni Adekunle Ajasin fi aiye silẹ?"} {"id": "3331#0", "text": "ọjọ meloo lo wa ninu oṣu August?"} {"id": "33551#0", "text": "Awon orile-ede wo lo sunmo Tunisia?"} {"id": "3545#0", "text": "Ọmọ ìlú wo ni òṣèré Genevieve Nnaji?"} {"id": "36841#0", "text": "Ile iṣẹ iroyin wo ni Funmi Iyanda ba ṣiṣẹ?"} {"id": "37663#0", "text": "Ẹlẹṣẹ wo ni a mọ si Cassius Clay?"} {"id": "37746#0", "text": "Ilu wo ni wọn bi Bobby Benson si?"} {"id": "38048#0", "text": "Ọdún wo ni Napoleon Bonaparte ṣ'alaisi?"} {"id": "38275#0", "text": "kí ni oluilu orile-ede Haiti?"} {"id": "4078#0", "text": "ṣe ipinle Ọṣun ni Ile Ife wa?"} {"id": "54948#0", "text": "ẹbun Grammy mélòó ni Mary J Blige ti gbà?"} {"id": "59455#0", "text": "ọdún wo ni Mariah Carey kọkọ gbé àwo jáde?"} {"id": "60238#0", "text": "Omo orile ede wo ni Li Lianjie?"} {"id": "60314#0", "text": "Ki ni orukọ ogbontarigi oṣere ti a mo si Baba Suwe ?"} {"id": "60391#0", "text": "Ki ni orukọ ile iṣẹ ti Dapo Abiodun da silẹ?"} {"id": "61267#0", "text": "Ilu wo lo tobi ju lọ ni orile ede Bulgaria?"} {"id": "62459#0", "text": "olorin wo lo kọ \"Billie Jean\" ?"} {"id": "62487#0", "text": "Ta ni ẹni tó dá Linux sílẹ̀?"} {"id": "62594#0", "text": "ọdún wo ni Bola Tinubu jẹ gomina Eko?"} {"id": "67530#0", "text": "Yunifasiti wo ni Dapo Abiodun ti ka'we?"} {"id": "67726#0", "text": "kí ni oluilu orile-ede South Sudan ?"} {"id": "67866#0", "text": "Kini oruko ṣọọsi ti David Oyedepo da silẹ?"} {"id": "67944#0", "text": "Ile-iwe eko giga wo ni Tam David West ti kawe?"} {"id": "68042#0", "text": "Ta ni ẹni tó ní ilé iṣẹ soundcity ?"} {"id": "68128#0", "text": "Iṣẹ wo ni Lizzy Anjorin ṣẹ?"} {"id": "68177#0", "text": "iru orin wo ni Fela Kuti kọ?"} {"id": "68257#0", "text": "Odun wo ni Frederick Fasheun ṣ'alaisi?"} {"id": "68382#0", "text": "Odun wo ni Aremu Gbadebo je Alake?"} {"id": "68412#0", "text": "Ta ni o da ile iṣẹ Daar Communications silẹ?"} {"id": "68449#0", "text": "Bawo ni awọn Hausa ṣe n ṣe Fura ti wọn?"} {"id": "68452#0", "text": "Ọdún wo ni wọn da ilé iṣẹ Facebook silẹ?"} {"id": "68729#0", "text": "Awon eya wo ni Ghana ni won sọ ede Akan"} {"id": "68921#0", "text": "Odun wo ni ogun Kiriji bẹrẹ?"} {"id": "69129#0", "text": "Ilu wo ni wọn bí Yvonne Nelson si ?"} {"id": "69146#0", "text": "Iṣẹ wo ni Aisha Buhari n ṣe??"} {"id": "69209#0", "text": "Omo orile ede wo ni William Onyeabor?"} {"id": "69258#0", "text": "Ibasepo wo lo wa laarin Oluremi ati Bola Tinubu?"} {"id": "69260#0", "text": "ilé iṣẹ iroyin wo ni Eugenia Abu bá ṣiṣe?"} {"id": "69301#0", "text": "Akọwe wo lo kọ \"Things fall apart\"?"} {"id": "69308#0", "text": "ọdún wo ni oba rilwanu Akiolu di ọba eko?"} {"id": "69396#0", "text": "Odun wo ni Botswana gba ominira?"} {"id": "69434#0", "text": "Kí ni orúkọ ilé iṣẹ ti Alhaji Razaq Ọkọya da silẹ?"} {"id": "70116#0", "text": "Ilu wo ni Moshood Abiola Politekniki wa?"} {"id": "70124#0", "text": "ọdun wo ni orile-ede Naijiria gba ominira?"} {"id": "70144#0", "text": "Ki ni oruko bibi osere Ade Love"} {"id": "70154#0", "text": "Ebun fiimu wo ni Nse Ikpe-Etim gba ni odun 2014?"} {"id": "70169#0", "text": "Awọn orukọ wo ni a n pe ni orukọ amutorunwa?"} {"id": "70186#0", "text": "Ọdún wo ni Ayo Fayose di gomina ipinlẹ Èkìtì?"} {"id": "70298#0", "text": "Omo ilu wo ni Kemi Adeosun?"} {"id": "70317#0", "text": "Ọdún wo ni òṣèré Rachel Oniga bẹrẹ sí ṣe eré itage?"} {"id": "70430#0", "text": "Odun wo ni Stella Obasanjo s'alaisi?"} {"id": "70487#0", "text": "Omo meloo ni Bose Ogulu bi?"} {"id": "70501#0", "text": "ọdun wo ni Teniade Aofiyebi kopa ninu fiimu Flower Girl?"} {"id": "70508#0", "text": "Ara ilu wo ni Lisa Omorodion?"} {"id": "70580#0", "text": "oṣere wo ni a mọ si Hubert Ogunde?"} {"id": "70588#0", "text": "awon fiimu wo ni Rosaline Meurer ti se?"} {"id": "70604#0", "text": "Omo orile ede wo ni Kamaru Usman?"} {"id": "70639#0", "text": "Ile iṣe wo ni Ugonna Umerou da silẹ?"} {"id": "70723#0", "text": "Ọmọ orile ede wo ni Kansiime Anne?"} {"id": "70727#0", "text": "onkowe wo lo kọ Igbo olodumare?"} {"id": "70760#0", "text": "Ibasepo wo lo wa laarin Tariro ati Emmerson Mnangagwa?"} {"id": "70931#0", "text": "Kontinenti wo ni Peru wa ?"} {"id": "71075#0", "text": "Ta ni o kọkọ jẹ aare orile ede Tunisia?"} {"id": "71133#0", "text": "Orile ede wo ni Kunqu Opera ti wá?"} {"id": "71225#0", "text": "Orile-ede wo ni wọn bi Elon Musk si?"} {"id": "71253#0", "text": "Awon oṣere wo lo se ere Love Castle?"} {"id": "71290#0", "text": "Odun wo ni Nana Akufo Addo je aare orile ede Ghana?"} {"id": "71301#0", "text": "Odun wo ni Erica Nlewedim kopa ninu ere Big Brother?"} {"id": "71355#0", "text": "Orile ede wo ni Sacramento wa?"} {"id": "71373#0", "text": "Orile ede wo ni ilu Ghadames wa?"} {"id": "7147#0", "text": "Agbegbe wo ni Eko ni Desmond Elliot n se asoju fun?"} {"id": "7148#0", "text": "ọdun wo ni wọn bẹrẹ Ẹbun Nobel?"} {"id": "9149#0", "text": "Ki ni oluilu ipinle Ọsun?"} {"id": "9505#0", "text": "Odun wo ni wọn bi akọrin Adekunle Gold?"} {"id": "9593#0", "text": "Kí ni orúkọ bibi akọrin Naira Marley?"}