| [ | |
| { | |
| "id": "calendar_001", | |
| "subset": "calendar", | |
| "question": "Tí òní bá jẹ ọjọ ajé, ọjọ wo ni ọjọ mewa òní yóò jẹ́?" | |
| }, | |
| { | |
| "id": "calendar_002", | |
| "subset": "calendar", | |
| "question": "Ọjọ àkọ́kọ́ nínú oṣù Ọ̀pẹ̀ ọdún yìí bọ sí ojo Ọjọ́rú. Ọjọ wo ni ètàdínlógún òní yóò bọ́ sí?" | |
| }, | |
| { | |
| "id": "calendar_003", | |
| "subset": "calendar", | |
| "question": "Ọjọ mẹrin mẹrin ni a máa n ná ọgà Dùgbẹ̀. Tí a bá ná ọjà náà ní ọjọ Ẹtì ní ọ̀sè tí ó kọjá, ọjọ wo ni ọjà náà yóò bo sí ní ọ́sè yìí?" | |
| }, | |
| { | |
| "id": "calendar_004", | |
| "subset": "calendar", | |
| "question": "Ọjọ mẹlòó ló wà nínú oṣù Agẹmọ?" | |
| }, | |
| { | |
| "id": "calendar_005", | |
| "subset": "calendar", | |
| "question": "Oṣù meloo ninu ọdún ni o ni ọgbọ̀n ọjọ géérégé?"" | |
| }, | |
| { | |
| "id": "calendar_006", | |
| "subset": "calendar", | |
| "question": "Ọjọ ọjà Owódé tí ó kọjá ni a bí Abebi. Ọjọ wo ni ọjọ tí a bí Abebi bọ́ sí tí òní ọjọ Ọjọ́bọ̀ bá jẹ́ ọjọ ọjà Owode míràn, tí a sì n ná ọjà náà ní ọjọ méfà mẹ́fà?" | |
| }, | |
| { | |
| "id": "calendar_007", | |
| "subset": "calendar", | |
| "question": "Ọjọ mẹlòó ló wà nínú oṣù Èrèlé" | |
| }, | |
| { | |
| "id": "calendar_008", | |
| "subset": "calendar", | |
| "question": "Ti ọjọ àkọ́kọ́ ọdun yìí bá bọ́ sí ọjọ Àbámẹ́ta, kínni ọjọ́ tí ó parí oṣù àkọ́kọ́ yóò jé?" | |
| }, | |
| { | |
| "id": "calendar_009", | |
| "subset": "calendar", | |
| "question": "Ti ọjọ àkọ́kọ́ ní oṣù Ògún b abọ si ọjọ Ìsẹ́gun, ọjọ wo ni ọjọ àkọ́kọ́ ní Oṣù Owewe yóò bọ́ sí?" | |
| }, | |
| { | |
| "id": "calendar_010", | |
| "subset": "calendar", | |
| "question": "Ti ọjọ àkọ́kọ́ nínú ọdún bá bọ́ sí ọjọ Àìkú, ọjọ Àìkú mélòó ni yóò wà nínú ọdún náà?" | |
| }, | |
| { | |
| "id": "calendar_011", | |
| "subset": "calendar", | |
| "question": "Ọ̀sẹ̀ mélòó ló wà nínú ọjọ́ mọ́kànlélógún? " | |
| }, | |
| { | |
| "id": "calendar_012", | |
| "subset": "calendar", | |
| "question": "̣̀sẹ̀ mélòó ló wà nínú ọjọ́ mérìndínlọ́gbòn?" | |
| }, | |
| { | |
| "id": "calendar_013", | |
| "subset": "calendar", | |
| "question": "Wákàtí mélòó ló wà nínú ìsẹ́jú ọ̀tàlélúgba?" | |
| }, | |
| { | |
| "id": "calendar_014", | |
| "subset": "calendar", | |
| "question": "Wákàtí mélòó ló wà nínú ìsẹ́jú ọgọ́sàn-án?" | |
| }, | |
| { | |
| "id": "calendar_015", | |
| "subset": "calendar", | |
| "question": "ìsẹ́jú mélòó ló wà nínú àáyá ọ̀tàlélọ̀ọ́dúnrún?"" | |
| }, | |
| { | |
| "id": "calendar_016", | |
| "subset": "calendar", | |
| "question": "Kínni ìlààrin wákàtí kan?" | |
| }, | |
| { | |
| "id": "calendar_017", | |
| "subset": "calendar", | |
| "question": "Kínni ìdá méjì ìsẹ́jú kan" | |
| }, | |
| { | |
| "id": "calendar_018", | |
| "subset": "calendar", | |
| "question": "Ọjọ́ mélòó ló wà ninu ọ̀sẹ̀ mẹ́ta?" | |
| }, | |
| { | |
| "id": "calendar_019", | |
| "subset": "calendar", | |
| "question": "Ọ̀sẹ̀ mélòó ló wà nínú oṣù mẹ́ta?" | |
| }, | |
| { | |
| "id": "calendar_020", | |
| "subset": "calendar", | |
| "question": "Oṣù mélòó ló wà nínú ọjọ́ ọgọ́sàn-án?" | |
| }, | |
| { | |
| "id": "calendar_021", | |
| "subset": "calendar", | |
| "question": "Ọ̀sẹ̀ mélòó ló wà nínú ọdún méjì?" | |
| }, | |
| { | |
| "id": "calendar_022", | |
| "subset": "calendar", | |
| "question": "̣̀Ọjọ́ mélòó ló wà nínú oṣù mẹ́ta?" | |
| }, | |
| { | |
| "id": "calendar_023", | |
| "subset": "calendar", | |
| "question": "Funke dé ilé Faderera ní aago mẹ́sàn-án alé ní ọjọ Etì. Tí ó bá lo wákàtí mérìndínlógójì ní ọ̀dọ̀ Funke, aago mélòó ni Funke padà sí ilé?" | |
| }, | |
| { | |
| "id": "calendar_024", | |
| "subset": "calendar", | |
| "question": "14. Ọkọ̀ ojúirin láti Osogbo lọ sí Kano yóò lo wákàtí èjìlélàádọ̀rin. Bimpe wọ ọkọ̀ náà ní aago méfà àbọ̀ àárọ̀ ọjọ Ọjọ́bọ̀ ní Osogbo. Tí ọkọ̀ náà bá ní ìdádúró ní Kaba fún wákàtí méta, aago mélòó ni Bimpe yóò dé Kano?" | |
| }, | |
| { | |
| "id": "calendar_025", | |
| "subset": "calendar", | |
| "question": "ìsẹ́jú àáyá mélòó ló wà nínú wákàtí mérin?" | |
| } | |
| ] | |