text stringlengths 3 3.37k | label stringclasses 3
values | language stringclasses 3
values | source stringclasses 3
values | domain stringclasses 3
values | split stringclasses 1
value |
|---|---|---|---|---|---|
ọkàn lára àwọn ọ̀dọ́ tó lọ ibi ìwáṣẹ́ àná ẹ lọ ka ọ̀rọ̀ rẹ̀ | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ọbàtálá ló ni ọ̀pá òṣooro ṣàngó àti ọ̀rúnmìlà ló ni àti | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Igba o lọ bi orere #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
...ṣùgbọ́n pé ọ̀run kan wà níbì kan, mi ò gbà á gbọ́, nítorí mi ò rẹ́ni tó kú rí tó padà wá sáyé pé òun kò rí ọ̀run wọ̀ ó. Ẹnìkan wà nílùú Ìjokò wa yìí, ó kú, ó wá ń padà wá sílé, ó wá ń bá ìyàwó ẹ̀ sùn, ó ń sanwó iléèwé àwọn ọmọ. Ìyàwó yẹn wáá bá mi pé... | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user: @user rara o kii se akeregbe emu"""" kí wá ni o? | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Eyin temi eku ojumo, emi eyan yin ogbeni Taofeek Omo Gawat Omo bibu ilu eko Ni Massey, Eko mi eko Ilé 🏡, eko Oni baje #Tweet… | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Aiye nreti eleya, Nibo lefi t'Oluwa si o #TweetinYoruba | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user Kú orí ire. Ọlọ́run á wò ó dàgbà. | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
#TweetinYoruba Saheed ni oruko mi,Sulaiman ni baba to bi lomo,abi mi si ilu Kano ni oke oya.Omo bibi ilu Ede ni mi ni ipinle osun | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user Ìgò epo méjì àti ọsẹ dúdú :)) | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Wọ́n ní ẹní bá ṣe ohun téèyàn kan ò ṣe rí, á rí ohun téèyàn kan ò rírí, ẹ ò ṣe fa ẹnibẹ́ẹ̀ lé Yáróbì lọ́wọ́? - #AjataOjo | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ǹjẹ́ o mọ̀ pé 1859 la ṣí ilé ìwé CMS Girama; ilé-ẹ̀kọ́ àkọ́kọ́ nílùú Èkó? #Yoruba #Njeomo https://t.co/QYeP2HEWGL | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user Ẹkú àtìlẹ́hìn o. Emi náa ti ṣẹ bẹ́ẹ̀. | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user Owe l'esin Oro,Oro l'esin owe,ti oro ba Sonu,owe laa fii wa.Dokita ise le se.#tweetinyoruba# | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ìpìlẹ̀ ère díída lẹ́yin ìgbèjàde rẹ̀ tó buru | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
aláàfin ké pe ológun gbogbo kárí ọ̀yọ́ bìní dahomey ẹ̀gbá òwu àti ifẹ̀ kí wọ́n bá òun mú ẹlẹ́mọ̀ṣọ́ | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Nijeria Kolomo kilo fomo e o Awon Boko Haram tun fee ji awon omoleewe gbe! Alaroye | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Nollywood ńṣe bẹbẹ!!!. . . . Eré yii sọ̀rọ̀ nípa àsà, ìbásepọ̀ ati ìdílé. Orísirísi, ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹ̀kọ́ ninu eré yii tí nkò lè sọ́ tán. | positive | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
RT @user: Congratulations on your trad 💝🥳 card also available in: #shona - Makorokoto emarooro #yoruba - Ẹ ku oriire ti igbeyawo… | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Yoruba ronu tí Bàbá Ogunde kò sì ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìtumò ni ayé òde òní. #TweetinYoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
mo wá rọ̀ ọmọ ẹ jẹ́ a jọ ti lẹ́yìn kí òtítọ́ bá lè jáde kí àwọn apànìyàn yìí fi imú dánrin ìjọba | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Ọ̀rọ̀ ìṣítí wa t’òní: ORÚKỌ OṢÙ NÍ YORÙBÁ (Our admonition for today: Name of months in Yorùbá) #yoruba #oroisiti #admonition… | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ire wa kò ní kọjáa wa | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
eje ki a fa le olorun lowo dokita lo so be agbenuso fun aare jonathan bugbeta lori oro bombu | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user Àṣà ìlú àti eégún náà ni. Bí ó ti ṣe wà láti ọjọ́ sí nìyẹn | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ọmọ Nigeria ìgbàlódé aláìlẹ́gbẹ́. . . . Aájò oni sinima àgbéléwò ti Nollywood ni tòótọ́ ìwà òṣèlú, ẹṣin àti ẹ̀yà nigbonni yìí, fún àwọn tó bá fẹ́ fikún òye wọn nípa ìdí tí a fi ni àwọn òkè ńláńlá lagbaye. Nípa báyìí, àwọn ìletò kereje ni orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí farahàn lónìí.. . . . Ẹ̀mí ọkàn fara hàn nínú ojutaye nít... | positive | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
walahi ti iya to bi mi ba toro ninu suya yii nko ni fun won je rara d | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
K'álára ó para mọ́, Àwa ọlọ́sà tí a ṣe ìlérí pé à ń bọ̀ wá ja ìlú yín yìí l'ólè l'óru àná, a kò le wá mọ́. Ó dùn wá díẹ̀. Ṣùgbọ́n ò-wí-bẹ́ẹ̀-ṣe-bẹ́ẹ̀ ni wá, à ń bọ̀ o. Kí tọmọdétàgbà má jáfira..."""" #OgunAwitele #Atelewo #Yoruba #YorubaBooks https://t.co/5lpcv9sjKh | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Orí mi tì mí lẹ́hìn, kí èrò mi di mímú ṣẹ. Ẹlẹ́dàá mi ṣe tèmi níre, lànà àràmàndà tuntun fún mi, Olódùmarè! | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: @user nso ojobi o, o fi koko se eran pepeye...... E ku ayeye ojo ibi aseyi samodun ninu ola ati ilera, igba odun, odun… | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ọ̀pẹ̀ orúkọ ọ̀rúnmìlà pọ̀ òun náà ni wọ́n á máa pè ní ẹ̀là ẹdú òbíríkítí afèdèfẹ̀yọ̀ àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user Ẹ̀yin ńkọ́? Kí ni ẹ rí ṣe? | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
in yorùbá dúkìá is property dúkìá wa ò ni jóná our property will not get burnt | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
You can only fetch water from a place that has a source for water. Níbi tí omi bá wà ní wón ti ń pọn #yoruba @user #Tefilah | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ibi lèkélèké ńgbé fọṣọ, ẹyẹ àparò ò lè mọbẹ̀. Elénìní ò ní mọ 'bi ayọ̀ọ wá wà, àlà lawọ̀, ọmọ èèyàn ò ní tapo si. O ò ṣ'àmín #Amin | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
èrè tí wọ́n jẹ lórí owó wa ni wọ́n fi njẹ̀jẹkújẹ | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ìtàn tó tayo. . Ẹ gbàgbé nípa àwọn alárìwísí, eléyìí jẹ́ Fíìmù ilẹ̀ adúláwọ̀ tó dára jùlọ ní ọdún yìí. O ní ìgberò gidi àti ṣíṣe Eré tóju ọ̀pọ̀lọpọ̀ lọ.Ìtàn tó dára jùlọ. | positive | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
ede geesi ni ko apileko yii sugbon use takuntakun ni international mother language day | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user Ẹṣé o. Ẹkú ìfẹ́ wa. Ọlọ́run Ọba á fi ìfẹ́ rẹ̀ han gbogbo wa o | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user Nǹkan tó ń dun àwọn nìyẹn àbí 🤣 | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Kí ni pẹ̀tẹ́lẹ̀? #Ibeere | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ẹnikan ki bu ṣango ni igba ẹrun | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user Ẹ dẹ́kun à ń ja owó ìpè lọ́nà àìtọ́. | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ÒǸKÁ NÍ YORÙBÁ / NUMBER IN YORÙBÁ (1): 10 - ẹ̀wàá 20 - Ogún 30 - Ọgbọ́n 40 - Ogójì 50 - Àádọ́ọ̀ta 60 - Ọgọ́ta 70 - Àádọ́rin 80 - Ọgọ́rin 90 - Àádọ́rùn-ún 100 - Ọgọ́rùn-ún 110 - Àádọ́fà 120 - Ọgọ́fà 130 - Àádóje 140 - Ogóje 150 - Àádọ́jọ | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Eré tó tayọ. Àwọn òṣèré náà kú ojú òsùnwọ̀n. Ìwòyè àti ètò eré náà dára púpọ. Orin eré náà tayọ. Ìtàn eré náà sì dára gidigidi. | positive | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
RT @user: Ọ̀rọ̀ òkèèrè, bí kò bá lé kan, yóò dín kan. / Words heard from afar, if they are not overstated, they will be understa… | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: @user Mo dupe Ife ti e fihan simi, a o ni gburo ibi si ara wa | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Nígbà t'ó ṣe, Ọọ̀ni Abewéilá fún àwọn ará Ọ̀yọ́-ilé lóko kan táwọn ẹyẹ àkọ̀ pọ̀ sí, ó yọ̀ǹda àyèe, agbègbè ti wọn fún wọn. #IjaIfeOyo | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user Iku ojiji lo ma de ba e o.ewo ni iwa palapala ti o fi owo @user te si iwe @user ? http://t.co/FqgLgg31cE | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Kí ni ìyàtọ̀ tó wà láàárín igún àti àkàlà? What are the differences between the buzzard and the vulture? #learnyoruba #Language #Yoruba #InYoruba #biodiversity #vultureculture #vulture… https://t.co/e0sj2GWbxh | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ẹni tí bíńtín ò tó, púpọ̀ yóò jìnnà sí i. / Abundance will be far from whoever is not contented with a little. [Contentment is it; it makes for increase.] #Yoruba #proverb https://t.co/Zwq2uZhTAB | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Olú means mushroom, head, leader (olú ilé iṣẹ́ wa - our head office) #Yoruba #InYoruba http://t.co/KqGneJSL8i | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user @user @user @user ohun to seni laanu ni wipe awa funra wa ko mo nipa ohun to je tiwa gaan | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Alákọ̀wé yín ń bẹ níhà ìlà-oòrùn London. Ní ẹ̀bá ibi tí àwọn ilé-ìfowópamọ́ àti ilé-iṣẹ́ ìfowóṣòwò parapọ̀ sí. | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Orí ni àwúre. Orí Máà padà lẹ́yìn mi. Máà jẹ́ kí n r'ówó sá, tilẹ̀kùn òṣì kí o ṣílẹ̀kùn ọrọ̀. Orí gbé mi délé owó, kí owó bá… | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
.@user were yin ti wa woja o! se asofin ipinle @user Afolabi Akanni ti ekigbe wipe DSS pa ko yi? https://t.co/p3wDPcXJ6I | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ẹ jẹ́ ká rántí aya ààrẹ wa #Patience #Jonathan nínú àdúrà wa. Kí Ọlọ́run báa ṣẹ́gun àìlera ara rẹ̀. | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Oke oke l'an lo ni ile Yoruba ati Nijeria lapapo https://t.co/aYuhQEIss6 | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ẹ kú Ọjọ́-Ọ̀sẹ̀ o gbogbo ọmọ #Oodua tòótọ́, ẹ̀yin ọmọ #Yoruba àtàtà, jákèjádò ilẹ̀-aye. Ṣé àlááfíà ni! | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Awa niyen o koda ayo nla gbaa ni""""""""@user: Ẹ kú àárọ̀ o. Ẹ sì sú ayọ̀ àná. #ekaaaro"""""""" | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: @user ko is nkan ti o nje ibunkun anobi o. Ibunkun Olorun a maa ba gbogbo wa gbe! | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user: @user """"""""se won bi sorin MO eja ni?"""""""" Edakun kini sorin? Cc @user @user @user @user""""""""Àṣìpa òwe | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: @user *atewo* *ijo* *ilu* *agogo* *sekere* mo ti so ibi ti mo ti un dana di ile ijosin | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ikú d'óró. Ikú ti pa ọ̀kan lára àwọn ògbóǹtarigi àgbáṣà àti èdè Yorùbá lárugẹ, bàbá Akínwùmí Ìṣọ̀lá ti di ẹni ilẹ̀. Ó di gbére, ó d'àrìnàk, ó dojú àlá. Sùn-un 're o!!! #Yoruba https://t.co/MxLr441wKt | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
9. Gbólóhùn mìíràn fún agbárí ni àtàrí, gbólóhùn mìíràn fún ọmọ kékeré ni aròbó, gbólóhùn mìíràn fún ìrètí ni_____ #Ibeere #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: @user asiko ojo lemi feran ni temi, ko ojo ro, ko ara tu oun gbogbo | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ojo ayo Ojo itura ni o n ro bayii, nise ni o dabi eni wipe ki n pada loo sun | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ọlọ́mọ ṣíkàtà ọba àgbàdo | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Emi fe moo!""""""""@user: Àwọn wo ni Yoòbá ń pé ní alábaraméjì? #ibeere #QnA #yoruba"""""""" | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ilu ibadan lale hmmm o ga o | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ìdí ìṣẹ́ ẹni la ti ń mọ 'ni lọ́lẹ. Má fòórọ̀ ṣiré ọ̀rẹ́ẹ̀ mi, tẹra mọ́ṣẹ́, ọjọ́ ń lọ! #Yoruba | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ogbeni biodun bashir to n sise pelu ajo universal basic education ube | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
16. Ọmọ awo ___ ní máa ń kí ara wọn ní """"""""o kú""""""""? A) Egúngún B) Ṣàngó D) Ògún #ibeere #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Awọn agbowode si tọ̀ ọ wá lati baptisi lọdọ rẹ̀, nwọn si bi i pe, Olukọni, kili awa o ha ṣe? O si wi fun wọn pe, Ẹ máṣe fi agbara gbà jù bi a ti rán nyin lọ mọ́. #jesus #bible #JayB #sangeberat #nigeriainfomcf #world #yoruba #language @user @user https://t.co/eTB0L3qDE2 | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ṣé epó tún ti hán ni? Ọkọ̀ ló pọ̀ lóríi ìlà ńlé epo yìí. Olúwa gbàkóso o #Nigeria | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
bí ebí bá pa ajé | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
6. Yàtọ̀ sí ká ná an, kíni a tún ń lo owó ẹyọ fún? #ibeere #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Ajé olókun Ògúgú lúsò Ajé onísò bòoji Asèwe dàgbà, Asàgbà dèwe Eni tí erú àti omo ñ fi ojojúmó wá kiri Ajé àgbà òrìsà, jé… | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
èdùà má finá ọmọ jó wa | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: @user Baba lo rò fún yoyo; l'ábé ògèdè l'ábé òronbó óti se d'ábé ata. | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: 2. Òtútù = òórùn, òrùlé = òòlé, ọ̀lẹ̀lẹ̀ = ọ̀ọ̀lẹ̀,_____ = oókọ. #Ibeere #Yoruba #learnyoruba #MotherLangaugeDay # | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user @user Oluwa maje Kari Ogun alantako. My #Yoruba people can relate to this @user | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Lẹ́yìn tí a bá ti pa ajá ìlú tán, ni ìdílé kọ̀ọ̀kan yóò tó pa ti rẹ̀ s'ójú ojúbọ Ògún ilé. A óò fi orí ajá tí a bẹ́ há ojú Ògún. #OsuOgun | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
15. Èwo ni kì í ṣe oúnjẹ ìbílẹ̀ Yorùbá? A) Gaàrí B) Kúlúkúlí D) Èbìrìpò #Ibeere #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
if delay is an action word say no to it this week nínú ọ̀sẹ̀ tuntun yìí ṣe ohun tí ó fẹ́ ṣe lásìkò láì jáfara kankan | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ọ̀yẹ́yẹ́ ló bí awo ire, Ọ̀yẹ́yẹ́ ló bí awo ìyè, awo tí ó dalẹ̀ á bálẹ̀ lọ. #NigeriaDecides2019 | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
sábó túnmọ̀ sí tuntun = lédè a ní sábó ní ó wà ní ìbàdàn ọ̀yọ́ ní bo ní sábó tí o mọ̀ ọ́ wà | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
WARA NA WA O. EXÚ WARA O. EXÚ WARANA WA KO MI O, EXÚ WARA O. BA MIWA IYAWO O, EXÚ WARA O. MA JE ORI MI O BAJE O, EXÚ WARA O. ME JE ILE MI ODARU. EXÚ WARA O AXÉ #exu #yoruba #batuquers https://t.co/qAiid99mP2 | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
The English call it LAKE Yorùbá á ma pè é ní ODÒ ADÁGÚN https://t.co/4gXnuRuZHm | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ní ọdún ni a fi àyájọ́ yìí lálẹ̀ àmọ́ ó di ọdún ọdún nínú oṣù kẹta ọdún ìgbìmọ̀ àjọ un ṣe ìpinnu wọ́n sì fi òtẹ̀ lu àbá lórí ojúṣe àwọn akọ́ṣẹ́mọṣẹ́ ní ti ìsòlúpọ̀ ìgbélárugẹ ìfàyàbalẹ̀ ara òye àti ìlọsíwájú | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
... Eni Tii A Koo Nii IKA ... Tii O Gba ... Ika N Bee Ninu Re Nii ...! #Yoruba. #OKAY. | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Aago yìí nílòo àtúnṣe. Aago márùn-ún ku ✔️ Aago márùún kù ✖️ @user #learnyoruba #Language #Yoruba https://t.co/8Fqjk6… | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ìbẹ̀jù Lekki ní Ìpínlẹ̀ Èkó, pẹ̀lú àwọn tí wọ́n ń ṣe gbíngbìn àti kíká àgbọn ní ọ̀pọ̀ yanturu, ní ilẹ̀ Yorùbá. Oko Igi àgbọn káàkiri gbogbo etí òkun rẹ̀. Ìbẹ̀jù Lekki náà ni wọ́n ń pa ẹja àti oúnjẹ òkun tí ó pọ̀ jù ní ilẹ̀ Yorùbá. | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Wọn tiẹ̀ ṣe eré náà dáradára, kò dùn, nkò lè sọ pé ó yẹ fún àkókò mi | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
Oríkì ma ń mú orí ẹni wú. #Oriki #Yorùbá | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
♫ èmi ganan ganan lèmi wọ́n ò ní fẹlòmíì ṣe mí ♫ | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Omo Yooba atata.RT @user: Ọmọ asòótọ́, ọmọ asánjú abẹ ní ìkó. Ẹ kú (cont) http://t.co/jAJe0EicZo | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
e wo foto ayeye igbeyawo omo ajimobi ati omo danguje nipinle kano fofo | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ìwúùre ati Àdúrà òwúrọ̀. #kaftantv #kaftantvyoruba #kaftan #yoruba #yorubaculture #yorubanimi #yorubalanguage #instagram #africa #african #nigeria #lagos #ekiti #ondo #ogun #oyo #ibadan https://t.co/OgZP5vlKsR | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
wọ́n á ní àjàgà bọ́ lọ́rùnun tàmẹ̀dù a kí ni àjàgà b kí ni à ń fi í ṣe | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Subsets and Splits
No community queries yet
The top public SQL queries from the community will appear here once available.