herwoww commited on
Commit
893cf10
·
verified ·
1 Parent(s): 96348a2

Upload folder using huggingface_hub

Browse files
Files changed (3) hide show
  1. README.md +15 -0
  2. yor_dev.csv +42 -0
  3. yor_train.csv +563 -0
README.md ADDED
@@ -0,0 +1,15 @@
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
1
+ ---
2
+ configs:
3
+ - config_name: yor
4
+ data_files:
5
+ - split: train
6
+ path: yor_train.csv
7
+ # - split: test
8
+ # path: yor_test.csv
9
+ - split: dev
10
+ path: yor_dev.csv
11
+ # - config_name: ara
12
+ # data_files:
13
+ # - split: test
14
+ # path: ara_test.csv
15
+ ---
yor_dev.csv ADDED
@@ -0,0 +1,42 @@
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
1
+ sentence,root,root_meaning
2
+ Mo fẹ́ràn iwò ojú rẹ púpọ̀,Iwò,spectacle
3
+ Owe Yoruba wipe àrò méta kìí d'ọbẹ̀ nù,Àrò,stone meant for cooking
4
+ Ogunleye pá ẹran igbẹ mẹ́ta lóru òní mọ́júmọ́,Ẹran,Meat
5
+ Ao bẹ ẹ̀sẹ̀ òbí lára ọmọ,Ẹ̀sẹ̀,SIN
6
+ Bàbá ṣe Ìrìnàjò lọ sí ibi tí Ará àwọn mọlẹbi wà,Ará,related people
7
+ Àgbọn tí ó wà ní orí igi náà kéré púpọ̀,Àgbọn,coconut
8
+ "Bí ọmọdé bá dá ẹ̀jẹ́,ọjọ́ náà ni mọ̀",Ẹ̀jẹ́,convenant
9
+ Ọ̀pọ̀lọpọ̀ irú ní jíjẹ má ń fọ ìdọ̀tí ojú,Irú,locust beans
10
+ Ajá tóyó kìí bá àìyó seré,Ajá,Dog
11
+ Ọmọ náà yọ ikun ní imú,Ikun,Mucus
12
+ Ifá kìí rí gbogbo nǹkan tán,IFÁ,god of divination
13
+ Afárá tí àwọn ọmọ ilé ẹ̀kọ́ ń gbà de ilé ẹ̀kọ́ wọn tí já,AFÁRÁ,BRIDGE
14
+ Ẹja ti ìwọ̀ mi gbe lo tóbi jù,Ìwọ̀,Hook
15
+ Ọbẹ̀ yìí tí ni ata jù,ỌBẸ̀,SOUP
16
+ Àrá san nígbà tí àwon akẹ́kọ̀ọ́ fi ọwọ́ gbe òjò,Àrá,thunder
17
+ Ife kan ni odiwon àgbo tí bàbá ṣe fún Dúpẹ́,IFE,CUP
18
+ Bàbá mi kò fi ọwọ́ sí kí n fẹ́ ẹ̀yà míràn ni ìyàwó,Ẹ̀YÀ,Tribe
19
+ Akintunde fi ìwọ̀ pa òjìjí méjì ni àn,ÒJÌJÍ,A LOCAL NAME OF A FISH
20
+ Olú ni ilé-ẹ̀kọ́ mi nínú gbogbo àwọn akẹgbẹ́ rẹ̀,OLÚ,SUPERIOR
21
+ Apá kejì fíìmù náà ni ìtàn náà parí sí,Apá,Hand
22
+ Ìwọ ati Adé ni yóò lọ fún ìdíje òlím,Ìwọ,You:
23
+ A le t'ori kí itọ́ tán lẹ́nu kí òrò tán,Itọ́,Saliva
24
+ Awọn olowo lo n ra aṣọ àrán nígbà tí o ṣẹṣẹ jade,Àrán,cloth
25
+ gbogbo igi oro ti ó wà ní àyíká yìí ti gbabode,ORO,A TYPE OF TREE
26
+ Ta ìrẹsì Ẹ̀kún rọ́bà fún ìyàwó mi,Ẹ̀kún,Fullness
27
+ Ẹ̀yìn ni Sọla joko sí,Ẹ̀yìn,Back
28
+ Egun hiha ni àwọn obìnrin jẹ fún àwọn ọkọ wọn,Egun,Bone
29
+ Àwọn àgbàlagbà ilé tí dá sí ọ̀rọ̀ náà,Ọ̀RỌ̀,WORDS
30
+ Opamade nífẹ̀ẹ́ sí ilà kẹ́kẹ́ ju àbàjà lọ,KẸ́KẸ́,A PECULIAR FACIAL MARK
31
+ Òógùn tí ó ń bọ̀ lára ẹ̀gbọ́n Olasode kò mọ ni kékeré,ÒÓGÙN,SWEAT
32
+ Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ se ìrìn-àjò lọ sí ibití àwọn ẹ̀yà ègùn wà,Ègùn,A tribe in Lagos
33
+ Àwọn ará ìlú Òdí yan alága tuntun,Òdí,A town in bayelsa
34
+ Agbọ́n ta mí ní oko lànàá,Agbọ́n,wasp
35
+ "Adewale ọmọ mi, ó gbọ́dọ̀ mo bí a ṣe ń tọju nkan ìní rẹ dáadáa, kí ayé má bà pé ọ́ ni ÀPÀ ọmọ",Apà,Spoiler
36
+ Oró inú ọmọ ènìyàn ó burú ju ti ejò lọ,ORÓ,"VENON, POISON"
37
+ Ìlú ọ̀fà ni mo ti ka ìwé,ọ̀fà,city in kwara state
38
+ Múra sí iṣẹ́ ọ̀rẹ́ mí má se ya ọ̀lẹ,Iṣẹ́,work
39
+ "Elubọ yìí kò kúnná tó, a ní láti fi ajọ̀ jọ̀ọ́",AJỌ̀,SIEVE
40
+ Mo fẹ́ ìtọ́ sí ònà fún ìgbéga,Ìtọ́,Guide
41
+ Ìran ti Aduke n wo lo ṣokunfa bi igbá náà se fọ,Igbá,Calabash
42
+ Kẹ̀kẹ́ bàbá àgbà kò ní ìjánu mọ́,KẸ̀KẸ́,BICYCLE
yor_train.csv ADDED
@@ -0,0 +1,563 @@
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
1
+ sentence,root,root_meaning
2
+ Ówo tí ó sọ mí ní igi imú ni kò jẹ́ kí n mi dáadáa,ÓWO,BOIL
3
+ Abọ́ ayọ́ ni ọmọ náà fi n jẹun,Ayọ́,Aluminum
4
+ Ní òwúrọ̀ kùtùkùtù ní mo já orín náà,Orín,chewing stick
5
+ kí ni wọn mú oyún wúndíá se ní òkò,Òkò,A town in Oyo state
6
+ Orogún ìyá Kọ́lá lo ràn-án lọ́wọ́,OROGÚN,RIVAL
7
+ Ere ṣíṣá ni iṣẹ́ ẹṣin,ẸSIN,HORSE
8
+ Wọ́n dá arákùnrin náà dúró sílé ìwòsàn ní torí ẹ̀ya ara rẹ̀,Ẹ̀ya,Tears
9
+ Ìdí tí Gboyega ko se wa sí ibi isẹ ko ye mi,Ìdí,Reason
10
+ Ẹ̀gbẹ́ Ọ̀TÚN ni ko jòkó sí,Ọ̀tún,right
11
+ Eku àgó mẹ́ta ni a bá nínú omi inú ada,ÀGÓ,A TYPE OF RAT
12
+ Obì inú kókó náà so púpọ̀,Obì,Colanut
13
+ Ọwọ́ ọmọ náà yá níbi ọ̀wẹ búbù,Ọ̀wẹ,MORSEL
14
+ Ọ̀TÙN jẹ ara olú ìlú ìpínlẹ̀ èkìtì,Ọ̀TÙN,A city in Ekiti
15
+ Ọ̀kan lára erè ìdárayá ni bọọlu gbigba wà,Eré,Play/Drama
16
+ Ọkan lára àwọn akọni ní lẹ̀ yoruba ni Ajagúnlá tí o tẹ ìlú ìlá do,Ìlá,a town in Osun state
17
+ "Èṣù ni Ogbẹni Akintọla yìí o, òun ni ó dá áwọ̀ sílẹ̀ láàárín Ọlá àti Ìbùkún",ÈṢÙ,DEVIL
18
+ okó ní ọmọkùnrin ń fi se ọkọ obìnrin,Okó,penis
19
+ Mo fẹràn ìlù púpọ̀ níbi àríyá,Ìlù,drum
20
+ Ẹ̀kọ jẹ́ oúnjẹ tí mo fẹràn jùlọ,Ẹ̀kọ,Local food derived from maize
21
+ OLORÌ ọba ìlú mi rẹ̀wá púpọ̀,OLORÌ,QUEEN
22
+ Àwọn Kẹ́kẹ́ kò jẹ́ kí a gbádùn igbá tí a gbìn rárá,KẸKẸ,A GRUB WHICH MAKES HOLES IN CALABASH
23
+ Ìlú Ọ̀rẹ̀ ni ìyàwó mi bímọ sí,Ọ̀RẸ̀,"A CITY IN ONDO STATE, NIGERIA"
24
+ Ìgbà ko tọ́ lọ bi orere,Ìgbà,Time
25
+ Gbogbo àwọn ọdẹ abúlé wa ti gbára dì láti kojú ìkokò ọdaju náà,ÌKOKÒ,HYENA
26
+ "Mo bẹ̀rù ọmọ náà púpọ̀, nítorí pé asa ni",ASA,TALKATIVE
27
+ Agbè yìí ti lu nìdí,AGBÈ,"BIG GOURD, NORMALLY USED BY PALM WINE TAPPER"
28
+ Ajá jẹ gbogbo egun náà tán,Egun,Bone
29
+ ọkùnrin tó sun rárà fún ọkùnrin ẹgbẹ rẹ̀,Rárà,A type of song/elegy
30
+ Àwọn àgbà ló lè yanjú ọ̀rọ̀ yìí,ÀGBÀ,ELDERLY PERSON
31
+ "Irọ́ ni Bola n pa fún àwọn òbí rẹ̀, ṣugbọn àbúrò rẹ̀ lo járọ́ rẹ̀",Járọ́,To expose a lie
32
+ Pí Padé ni ilẹkun ilé iṣẹ́ wà di bí a ṣe ń sọ̀rọ̀ yii,PADÉ,"TO SHUT, TO CLOSE UP"
33
+ Ó ti rẹ ẹyẹ agbe yìí débi wípé kò lè fò dáadáa mọ́,AGBE,A TYPE OF BIRD
34
+ Iya àgbà ran Fọlákẹ́ ni Erèé l'ọja,Erèé,Beans(coupea)
35
+ Baba gbìyànjú láti ré ègún kúrò lórí àwọn ọmọ,Ègún,"Spell, curse"
36
+ Olóyè jagun gbìyànjú láti dáàbò bo ìlú rẹ,Jagun,A military title
37
+ Ẹranko kò ní ohun méjì tí o fi ń se agbára kọjá ìwo,Ìwo,Animal horn
38
+ Ókéré gbádùn ẹyìn jíjẹ,Ẹyìn,palm tree fruit
39
+ Ọ̀ọni fi ìrù rẹ na ẹkùn ní ojú,Ìrù,tail
40
+ "Tí ẹ kò bá sà àwọn isẹpẹ igi náà dáadáa, ebè kíkọ náà kò ní yá",SÀ,PICK
41
+ "Ní aláìsí ìṣẹ̀lẹ̀, kì í sí ìtàn",ÌTÀN,STORY
42
+ Ẹ̀re agbabọ́ọ̀lù náà wà ní pápá ẹgbẹ agbabọ́ọ̀lù rẹ̀,Ère,Statue
43
+ Owò tí ènìyàn ba mọ ni kí ó tẹra mọ́,Owò,business
44
+ Ọmọ náà ní ẹ̀jẹ̀ púpọ̀ lára,Ẹ̀jẹ̀,Blood
45
+ "Ọjọ́ tí ẹ bá lọ sí oko, ẹ dákun ẹ bá mi gé okùn agba bọ̀",AGBA,A TYPE OF ROPE FOUND IN FOREST
46
+ ìyá ran ọmọ ní Abó ni oja,Abọ́,plate
47
+ Ọ̀wẹ tí ẹnu rẹ bá gbà ní kí ó máa bù,Ọ̀wẹ,MORSEL
48
+ Ẹ sáré bá Ìyá Ìtùnú mú ife kan wá,IFE,CUP
49
+ Lọ sun ilẹ̀ tí mo gbé sí èyìnkùlé,Sun,To burn
50
+ Ọmọ ìlú Òró ni ìyàwó mi,ÒRÓ,"A CITY IN KWARA STATE, NIGERIA"
51
+ Egbò náà tí di ọyún sí inú gan-an ni o,ỌYÚN,TUMOR
52
+ Àwọn amọ̀kòkò pọ̀ ni abúlé wa,ÌKÒKÒ,CLAY RESERVOIR
53
+ Inú igbó ní wón sin òkú ẹni ti o bá ní iké sí,Iké,hunchback
54
+ Mo bẹ̀rù awọn ọmọ bẹrẹ púpọ̀,BẸRẸ,"AN AREA IN IBADAN, OYO STATE"
55
+ Àwọn Agbè-fún-ọba rí pé àwọn doọ̀là àwọn ọmọ ìlú lọ́wọ́ àwọn ọdanran ni ÀYÈ,ÀYÈ,ALIVE
56
+ Ọjà ni Ade ti bá ọrẹ rẹ atijọ pade,Ọjà,market
57
+ Mo ti fi ìgbà kan jẹ ejò ỌKÁ rí,ỌKÁ,COBRA
58
+ Àwọn olórin fẹràn Abo púpọ̀,Abo,Female
59
+ Ilé-Ifè ni ìran Yorùbá ti sẹ̀ wá,IFẸ̀,A TOWN IN OSUN STATE NIGERIA
60
+ Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ní kó Ẹ̀kọ́ nípa ìmọ̀ síáyẹ́nsì,Ẹ̀KỌ́,Knowledge
61
+ Bàbá naa jẹ́jẹ̀ pe awon kòní na ọmọ náà,Jẹ́jẹ̀,To make a vow
62
+ Ilà kẹkẹ dára ní ẹ̀kẹ́ Yéwándé gidigidi,KẸ́KẸ́,A PECULIAR FACIAL MARK
63
+ Àgbẹ̀ náà fí inú oko rẹ kí àwọn irú náà le dínkù,Irù,tsetse fly
64
+ Olóńgbò tó jẹ́ ẹja mi lo jẹ́ kí n jẹ Àmàlà mi ni àsán,ÀSÁN,EATING FOOD WITHOUT ADDING FISH/MEAT
65
+ Ìgbà tí Bola jẹun tan ni o sun,Ìgbà,Time
66
+ mo nífẹ̀ẹ́ sì ẹran ògúnfe ni jíjẹ,Ẹran,Meat
67
+ ÀPÀ ọmọ kìí ni dúkìá tó ní láárí kan pàtó,Apà,Spoiler
68
+ Mo nífẹ̀ẹ́ sí kíkọ́ èdè Ẹ̀GBÁ,Ẹ̀GBÁ,NAME OF A TRIBE IN YORÙBÁ KINGDOM
69
+ Njẹ o ma wá sí ilé ikẹkọ ní ọ̀la,Ọ̀la,tomorrow
70
+ Gágá ni ọnà há ni ẹnu ọnà abawole sile igbagbo náà,Gágá,Tightly
71
+ Ẹ jẹ́ kí a bọ̀wọ̀ fún Ọ̀gá wa dáadáa,Ọ̀GÁ,MASTER
72
+ Ẹní àrá bá pa kìí sun silẹ,Àrá,thunder
73
+ Diẹ loku ki ọmọ jabọ́ lẹyìn ìyá ìkókó nígbà tí ọ̀já rẹ tu lojiji,Ọ̀já,Rapper to mount baby
74
+ Ẹyẹ agbe mẹ́ta ni mo ṣe alabapade lọ́nà oko,AGBE,A TYPE OF BIRD
75
+ Èdè ni o ma ń sọ ìran tí ènìyàn ti wá,Èdè,Language
76
+ Wọn pe ẹranko tó ní ìwo ìgbín yọjú,Ìwo,Animal horn
77
+ Àwọn Agbè-fún-ọba ní láti pàdé ni ìlú Ìbàdàn,PÀDÉ,TO COME TOGETHER
78
+ Rí dájú pé o pe ògèdè sí oúnjẹ kí o jẹ́,Ògèdè,incantation
79
+ Àṣà radarada gbáà ni kí ènìyàn máa rin ní ìhòòhò,ÀṢÀ,CULTURE
80
+ òkúta tí ọmọ náà jù ORÍ ni o ti bá ewúrẹ́,ORÍ,
81
+ Gbé ìkòkò náà bá mi ní ọ̀dẹ̀,Ọ̀DẸ̀,PASSAGE
82
+ Àgbò tí ìwo rè bá sẹ́ kò se pa iléyá,Ìwo,Animal horn
83
+ Ọdẹ pa ikún jẹ ní oko,Ikún,A kind of Squirrel
84
+ Owó ní àkàndùn ti mu ọmọ náà,Ọwọ́,Hand
85
+ Ẹṣin ọba ìlú ìgbẹ́kẹ̀lé kú ní àná,ẸSIN,HORSE
86
+ Ẹyin meji ni Ade fi sori ounjẹ rẹ̀,Ẹyin,Egg
87
+ ỌSÁN ìlù náà já nígbà tí akọrin lòó,Ọsán,One of the rope used to tie talking drum
88
+ Akinola n sáré gẹ́gẹ́ bíi ẹ́gbọ́n rè,Gẹ́gẹ́,Exactly
89
+ "Ẹ̀tù, ọta ati ààyá ni o wà nínú ìbọn ọdẹ náà",Ààyá,
90
+ Ọ̀rọ̀ ẹnu Alarape kò dára tó,Ọ̀RỌ̀,WORDS
91
+ Bàbá mi lo kọmi bí a ṣe ń ṣe Ẹ̀TÙ,Ẹ̀TÙ,GUN POWDER
92
+ won ti gbe igbá ọsẹ le ọmọ náà lórí ki àṣírí to tu,Igbá,Calabash
93
+ Ọbẹ̀ ilá dara fún Ọkùnrin tí àtọ̀ rẹ sàn,Ilá,Okro
94
+ Àdá ni ó fi pa ẹranko ẹhànnà náà,ÀDÁ,CUTLASS
95
+ "Ọjọ́ tí mo bá tún rí ọ pé o ṣe agbe, mo máa nà ọ́",AGBE,BEGGING
96
+ Àlàmú ni oríkì tí ìyà àgbà fún un mi,ÀLÀMÚ,A MALE NAME
97
+ Gba ìparí yìí kí o máa fi ra Ekundayọ lórí,ÀWÙJẸ̀,SOFT SPOT
98
+ Kòsí ààyá kankan nínú ìbọn bàbá ọdẹ náà mọ́,Ààyá,
99
+ Rí dájú pé o lọ sí ilé ìtọ̀ kí o tó sùn,Ìtọ̀,Urine
100
+ Gbogbo Igbìyànjú Awẹle láti di aya ni ọ̀dẹ̀ Àyànwande lo jásí asán,ASÁN,VAIN
101
+ Ile ẹ̀kọ́ gbogbo nise ti ìlú ìré ni Ariyọ̀ ti kàwé,Ìré,"A town in Osun State, Nigeria"
102
+ Ègún ìdílé kò ní sẹ lórí gbogbo wa,Ègún,"Spell, curse"
103
+ Mo fún ọmọ ní igba náírà lá ti fi jẹun,Igba,two hundred
104
+ "Ẹnití a bá torí tiẹ̀ pa adìẹ, iwe ló máa ń jẹ́",IWE,GIZZARD
105
+ Àná ni ọjọ́ìbí mi,Àná,yesterday
106
+ Inú òkùn ni mo bá Sọlápé nigba ti mo dé ilé wọn,Òkùn,Darkness
107
+ Ọkàn lara ọjà to gbajugbaja ni ọjà Gbági ni ìlú Ìbàdàn jẹ,Ọjà,market
108
+ Bọọlu náà ti kọjá ìlà ki adari ayo to fan fere,Ìlà,line
109
+ Ètò ìṣúná fún àwọn odi wà lára ohun tí ìjọba mẹnu bà,Odi,dump
110
+ Ẹ̀yìn ni olukọ ti na akẹkọ náà,Ẹ̀yìn,Back
111
+ Ogún àpò ẹ̀wà kò lé tó wa lò níbi ìnáwó òkú ìyá àgbà,OGÚN,TWENTY
112
+ ìjọba kọ́ ilé ìwé ìgbàlódé sí ìlú Òdí,Òdí,A town in bayelsa
113
+ "Oṣù tó ń bọ̀, ní ọ̀wẹ̀ yóò kàn mí",Ọ̀wè,A COMPANY SUMMONED TO ASSIST ONE OF THEIR MEMBER IN MANUAL LABOR
114
+ "Ẹ̀sín tí wèrè yóò ṣe, kìí jẹ́ kí ó kú bọ̀rọ̀",Ẹ̀SÍN,SHAME
115
+ Pátákó yìí kò sí fún kíkọ ikọkukọ,PÁTÁKÓ,"PLANT, BOARD"
116
+ "Èṣù má ṣe mí, ọmọ ẹlòmíràn ni kí o ṣe",ÈṢÙ,DEVIL
117
+ Ẹkùn jẹ́ ọ̀kan lára ẹranko tó rẹ wà,Ẹkùn,Leopard
118
+ Ẹja nla ni ìwọ̀ ọmọ náà gbé,Ìwọ̀,Hook
119
+ Akinyemi se ọgbà fún àwọn ẹran rẹ̀,Ọgbà,Garden
120
+ Ogunleke mú ejò ọkà wá sí inú abúlé ni ÀYÈ,ÀYÈ,ALIVE
121
+ Ọmọ tí ntà ÒRÍ kiri kọjá ní òwúrọ̀,ÒRÍ,Shea Butter
122
+ Àwọn agbófinró fi ìpá dára sí ọ̀daràn náà lára,ÌPÁ,KICK
123
+ Ojú egbò náà nílò ìtọ́jú gidigidi,EGBÒ,WOUND
124
+ Itan ni Mobolaji fi ṣèse níbi ìjàmbá ọkọ̀,ITAN,THIGH
125
+ Ìkokò ńlá kan wà ní agbègbè oko wa nígbà kan,ÌKOKÒ,WOLF
126
+ Ẹṣin Ọba ti fi pátákò rẹ gbá akódà lẹ́nu,PÁTÁKÒ,HOOF
127
+ "Ìjì kìí jà, kí ó dà omi inú àgbọn nù",ÌJÌ,STORM
128
+ Olùkọ́ náà fẹ́ràn láti máa mú Egba dání,ẸGBA,CANE
129
+ A ní láti bẹ̀rẹ̀ díẹ̀ kí a lè rí ọ̀nà náà gbà,BẸ̀RẸ̀,BEND
130
+ Ara kìí ṣe òkúta ni awọn yorùbá wí,Ara,Body
131
+ Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ mọ odi nítorí Àbò,Àbò,Security
132
+ "Ọ̀rọ̀ tí a jọ sọ ní àná, ó ti di ọ̀rọ̀ awo o",AWO,SECRET
133
+ Àgbẹ̀ tí ó lọ sí oko tí kò mú ọkọ́ lọ́wọ́ eyín rẹ̀ ni yíò lò,Ọkọ́,Hoe
134
+ Adesola sá àsálà fún ẹbọra búburú náà,SÁ,RUN AWAY
135
+ Àwọn Oladele pa ỌKÁ ńlá kan ní ọ̀sán yii,ỌKÁ,COBRA
136
+ "Díẹ̀ loku ki n tẹ ejò paramọ́lẹ̀ mọ́lẹ̀, nitori ọgba ni àwọ̀ rẹ̀ ati erupẹ ilẹ̀",Ọgba,Equal
137
+ Solape gbọ́dọ̀ dé ìlú Ọ̀yun ni kùtùkùtù ọlá,Ọ̀YUN,A TOWN IN KWARA STATE
138
+ Igi osè pọ̀ nínú oko Baba bàbá mi,OSÈ,A TYPE OF TREE
139
+ Wo ẹ̀gbẹ́ Ọ̀TÚN rẹ kí o gbé baagi rẹ,Ọ̀tún,right
140
+ A ní láti sà àwọn ìdọ̀tí ẹ̀wà náà dáadáa,SÀ,PICK
141
+ Aràn n yọ ọmọ náà lẹnu,Aràn,worm
142
+ Ọ̀gá wa ti ń bọ̀ wá sí yàrá ikawe,Ọ̀GÁ,MASTER
143
+ Àwọn Talabi ni ṣíṣe ni Ìpínlẹ̀ ògùn ni oṣù tó ń bọ̀,ÒGÙN,A STATE IN NIGERIA
144
+ Ìlú Ọ̀TÙN rẹwà púpọ̀ láti gbé,Ọ̀TÙN,A city in Ekiti
145
+ "Àrò yẹ nígbà tí Bọ́lá n dáná lọwọ, ọbẹ sì dànù",Àrò,stone meant for cooking
146
+ Gbogbo àgbọn tí mọ rà ní ọjà lo tí bàjẹ́,Àgbọn,coconut 🥥
147
+ Ìlú Ọ̀yun rọrùn láti gbé púpọ̀,Ọ̀YUN,A TOWN IN KWARA STATE
148
+ Ẹyẹ idì náà gbé ọmọ Adìẹ,Idì,Eagle
149
+ Àwọn oníṣòwò ìkòkò a máa jèrè púpọ̀ ní ayé àtijọ́,ÌKÒKÒ,LOCAL POT
150
+ gbogbo igi afàrà inú oko baami tí dawo tán,Afàrà,Shingle wood
151
+ olùkọ́ àgbà ra ọkọ̀ fún ìyàwó rẹ̀,Ọkọ̀,CAR
152
+ Gbogbo ilé kí bàbá kú Àbò,Abọ̀,welcome
153
+ Ejò isán jẹ́ ejò olóró tí ó burú púpọ̀,ISÁN,A TYPE OF SNAKE (WHICH LIKE SLEEPING)
154
+ "Láti le tesiwaju, a nílò ìfẹ́ aisẹtan láàárín wa",ÌFẸ́,LOVE
155
+ Àwọn agbábọ́ọ̀lù jẹ́jẹ̀ atilẹyin wọn fún akọ́nimọ̀ọ́gbá tuntun,Jẹ́jẹ̀,To make a vow
156
+ Ìkokò kì í fi eegun já afira,ÌKOKÒ,WOLF
157
+ Kúnlé ra asọ fún àwọn Òbí rẹ̀,Òbí,parent
158
+ òkò tí a sọ mọ ọ̀pẹ ni ọ̀pẹ ṣọ mọ́ ni,Òkò,stone🪨
159
+ "Ẹnití ó bá gbé ọkàn lé Ọlọhun, yóò ní ìyè àìnípẹ̀kun",ÌYÈ,LIVE
160
+ Ó gbọ́dọ̀ ṣe Ẹ̀rán orin náà dáadáa kí ó tó lè dán mọ ọ lẹ́nu,Ẹ̀rán,Something not to forget
161
+ Bí èniyàn kò bá dé oko bàbá ẹnìkan kò le mọ̀ bí o ti fẹ̀ tó,Oko,farm
162
+ Gbogbo ìlú lé arákùnrin náà sí ẹ̀yìn ìlú ní torí wípé iké tí o ní,Iké,hunchback
163
+ Òní ni owo ọ̀yà yín yóò jẹ́ sísan,OWÓ,Ọ̀YÀ
164
+ Ọmọ kékeré kan bú sí Ẹkún láàrín ojú ọ̀nà,Ẹkún,Cry
165
+ Adekunle fẹ́ràn kí ó máa jẹun ní orí òró,ÒRÓ,STAND
166
+ Àwọn ará ìlú feyikọgbon fẹ́ mọ ìdí ọrọ̀ Agbaakin ìlú naa,ỌRỌ̀,WEALTH
167
+ Ọta tán nínú ìbọn awọn olè náà ni wọn bá fi ẹsẹ fẹ́ ẹ,Ọta,Bullet
168
+ Ọ̀pọ̀lọpọ̀ eegún ló wà níbi ayẹyẹ ìfinijoyè,Eegún,masqurade
169
+ igi oro ti wó lulẹ,ORO,A TYPE OF TREE
170
+ Ìkà ni olópàá to yinbọn mo ọmọ náà,Ìkà,wicked
171
+ Ipa wo ni ìwọ là kalẹ̀ fún ọjọ́ iwájú àwọn èwe,IPA,PATH
172
+ ìlù bàtá ni wọn lù ni ọjọ́ìbí mi,Bàtá,a type Drumbeat
173
+ Ara àwọn ìlú tí o jẹ́ gbaju gbaja ni ìlú ìwó jẹ́,Ìwó,A town in osun state
174
+ Kò sí bí àna se kéré tó àna ni àna yíò ma jẹ,Àna,inlaw
175
+ Ìkà ni Kunle ti o lẹ okuta mo ọrẹ rẹ,Ìkà,wicked
176
+ Eku àgó náà tí lu Pakute,ÀGÓ,A TYPE OF RAT
177
+ Ìlú Ọ̀yọ́ ni mo gbé dàgbà,Ọ̀YỌ́,A STATE IN NIGERIA
178
+ Bàbá aláwò sọ fún àwọn adigun jalè náà pé kí wọn lọ wa Osé Sango wá,OSÉ,A TOOL USED BY SANGO WORSHIPPERS
179
+ Aya mi mọ iyán gún,Aya,Wife
180
+ Bi ara kò bá rọ OKÙN ara kòlè rọ adiẹ,Okùn,Rope
181
+ Àwo mẹ́jọ ni ìyá àgbà sọ wípé mo fọ nígbà tí mo wà ní kékeré,ÀWO,PLATE
182
+ Ìjọba gbọ́dọ̀ maa san owó ọ̀yà àwọn òṣìṣẹ́ ni kété tí oṣù bá ti parí,OWÓ,Ọ̀YÀ
183
+ Òjò tí ó rọ̀ ni àná tí ṣiṣẹ́ ìyè fún igi náà,ÌYÈ,LIVE
184
+ Ṣé o lè tẹ́lẹ̀ mi de Ọ̀rẹ̀ ni Ọ̀tunla,Ọ̀RẸ̀,"A CITY IN ONDO STATE, NIGERIA"
185
+ ìyàwó tí wọ́n fẹ́ láìpẹ́ yìí ti bí ọmọ,Ọmọ,child
186
+ Àìsàn ibà ni Ẹ̀fọn máa ń fà lára,Ẹ̀FỌN,MOSQUITO
187
+ Ẹ gbé ẹrù náà sí Igun ilé ìdáná,IGUN,CORNER
188
+ "A nílò isan ni ori ọmọdé, kí a lè gba ibẹ fún ní abẹ́rẹ́",ISAN,VEIN
189
+ Isan méjì ni àwọn dókítà sọ pé ó já ní ọwọ́ ọmọ ganfe naa,ISAN,VEIN
190
+ Adewolu ni àyò bàbá rẹ̀,ÀYÒ,FAVORITE
191
+ Ẹfọ̀n kúrò ní ẹran àfi Pakute pa,ẸFỌ̀N,BUFFALO
192
+ Ọmọ bíbí ilú ìlá ni oga ọlọ́pàá lorile ede Nigeria tẹlẹ rí,Ìlá,a town in Osun state
193
+ Ilé ọlá dára púpọ̀ láti gbé,Ọlá,wealth
194
+ Ọwọ́ tẹ awọn olè ti wọn n da ilu Ọ̀tà láàmú,Ọ̀tà,"A town in Ogun State, Nigeria"
195
+ Ẹni tí ó ni èkù lo ni ọ̀bẹ,ÈKÙ,CUTLASS/KNIFE HANDLE
196
+ Ọpẹ́ tí ẹ dá yẹn kéré jọjọ,ỌPẸ́,THANKS
197
+ Ọ̀já kan ṣoṣo tí ìyá Ìbejí rà logo pọn àwọn ọmọ rẹ mẹrẹrin,Ọ̀já,Rapper to mount baby
198
+ ọdún kẹta nìyí tí mo ti ń lo ajọ̀ mi,AJỌ̀,SIEVE
199
+ Igbà lo já ti akọ̀pẹ náà se kan,Igbà,rope use to climb palm tree
200
+ Mo Sùn ní èbá ọ̀nà lànà,Sùn,Sleep
201
+ Mọ gbàgbé láti ranmi létí ní ọ̀la,Ọ̀la,tomorrow
202
+ "Bí ògiri Adio kò bá lanu, aláàmù Olusegun kò lè wọ ibẹ",ALÁÀMÙ,LIZARD
203
+ Ire ni ojú owó n rí,Ire,Goodness
204
+ Agbe sise kò yẹ ọmọlúwàbí rárá,AGBE,BEGGING
205
+ Fi ÒRÍ pa ara rẹ kí ó má dàn-án,ÒRÍ,Shea Butter
206
+ Mo rán ọmọ ní Obì àti orógbó,Obì,Colanut
207
+ ọkọ́ jẹ́ ọ̀kan gbóògì nínú irinṣẹ́ àgbẹ̀,Ọkọ́,Hoe
208
+ Ìjì tí ó jà ní alẹ́ àná ni agbára púpọ̀,ÌJÌ,STORM
209
+ Igi Osè kì í pẹ́ gbabode,OSÈ,A TYPE OF TREE
210
+ Adesoji kò mọ iye owó tí ó kó pamọ́ mọ́,IYE,NUMBER
211
+ "Àwọn olórin fi ijo sí, nígbà tí àwon oníbàtá dá wọn lára mi",Bàtá,a type Drumbeat
212
+ Rí dájú pé o fọ ẹsẹ̀ kí o to wọlé,Ẹsẹ̀,leg
213
+ Ọwọ́ Bukola ni orógùn yìí tí kán sí méjì,ORÓGÙN,"TURNING STICK, TURNER"
214
+ Opamade nífẹ̀ẹ́ sí ilà kẹ́kẹ́ ju àbàjà lọ,KẸ́KẸ́,A PECULIAR FACIAL MARK
215
+ Kabiyesi náà fí olá jiyọ̀ láàfin,Ọlá,wealth
216
+ Gbogbo nkan há gágá fún Adé bíi ọjọ mẹta sẹyìn,Gágá,Tightly
217
+ Yorùbá ní ìṣẹ́ kìí déédé ṣẹ bí o bá nídìí,Ìṣẹ́,poverty
218
+ Ọ̀mọ tí wọ́n lò lára ilé náà kòtó,Ọ̀mọ,A builder of wall
219
+ Ọbẹ̀ ẹyìn dun jẹ iyán,Ẹyìn,palm tree fruit
220
+ Mọ fe ra agbọ̀n ní ọjà ní ọlà,Agbọ̀n,Basket
221
+ Ilà àbàjà ni won nkọ ni ilu Òwu,Ilà,triber mark
222
+ Ogun kò dà bí iyán àti ẹ̀kọ́,OGUN,WAR
223
+ àpò ògùn apa Ẹ̀fọn dára láti máa fi sùn,Ẹ̀FỌN,MOSQUITO
224
+ Máa ṣọ́ra láti bá Àbẹ̀ọ́ rìn nítorí ìwà,ASA,TALKATIVE
225
+ Kẹkẹ tí ba gbogbo igba oko Solape jẹ́,KẸKẸ,A GRUB WHICH MAKES HOLES IN CALABASH
226
+ Ago mélòó ni ìdíje náà yóò bẹ̀rẹ̀,AGO,CLOCK
227
+ Ẹ bá mi rántí mú Awò mi bọ̀ nínú yàrá,AWÒ,SPECTACLE
228
+ Fi Abó bu omi wá,Abọ́,plate
229
+ Ajá tí yóò sọnù kòní gbọ́ fèrè ọlọ́dẹ,Ajá,Dog
230
+ Ìtẹ́ Ọ̀kẹ́rẹ́ náà járọ̀ nígbà tó jábọ́,Járọ̀,To break a fall
231
+ Ìyá mi nílò Àyè tí ó gbòòrò fún ọjà wọn,ÀYÈ,SPACE
232
+ Ìwó tí o ni ilẹkùn ti o ni kọ́kọ́rọ́ ni wọ́n ki oríkì àwọn ọmọ ìpínlẹ̀ naa,Ìwó,A town in osun state
233
+ Mo lọ sí ọjà ni àná,Àná,yesterday
234
+ Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ta ẹyẹ ní ỌFÀ,Ọfà,catapult
235
+ Mo fẹ́ lọ sí ilé ìtọ̀ láti to,Ìtọ̀,Urine
236
+ Ẹkún ìyàwó jẹ́ ọ̀kan gbóògì nínú àṣà yorúbá,Ẹkún,Cry
237
+ Ọrẹ títa nínú oṣù lamulana dára púpọ̀,ỌRẸ,ALMS
238
+ Abẹ́ ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ ni ìlú ìbàdàn wà,Ìlú,Village
239
+ Kunle àti Ṣọla jọ kanko asọ àrán lo s'ode,Àrán,cloth
240
+ Ọ̀rẹ́ mi àtàtà ni Kolawole àti Taofiki,Ọ̀RẸ́,FRIEND
241
+ "Ẹyin akẹ́kọ̀ọ́ mi, ẹ rí dájú pé ẹ ka àwọn ewì yín dáadáa, Ẹ̀RÁN ni ó jẹ fún yín ooo",Ẹ̀rán,Something not to forget
242
+ "Inú kò gbọ́dọ̀ bí Baba aláwò, kí ó fi ajá bọ ifá",IFÁ,god of divination
243
+ Ẹ̀KỌ̀ ẹlẹ́kọ̀ ni ẹ̀gbà ẹlẹ́gbà,Ẹ̀KỌ̀,Abandoned
244
+ Ọmọ ìlú Ọ̀la ni alaga tuntun ni ìjọba ìbílẹ̀ rẹ,Ọ̀LÀ,a town in Osun State
245
+ Ilá pele ti Ṣọla ko ni aburo baba re fi dá mọ̀,Ilà,triber mark
246
+ Ẹ̀yà ni o ma ń fi ìran kan yàtọ̀ sí òmíràn,Ẹ̀YÀ,Tribe
247
+ Ayò ọlọpọlọ gbáà ni ayò ọlọ́pọ́n,AYÒ,GAME
248
+ "À-kúkú-bí, ó sàn jù kí ènìyàn bí ọ̀dẹ̀ ọmọ lọ",Ọ̀DẸ̀,IMBECILE
249
+ idanilẹkọ yóò wáyé lọla nipa aràn,Aràn,worm
250
+ Àwọn ọmọ ile-iwe náà bu ọ̀wọ̀ fún akẹgbẹ won to se dáadáa nínú ìdíji oníléjilé,Ọ̀wọ̀,honour
251
+ ọ̀gọ̀rọ̀ àwọn odẹ ló sun rárà ní bi igbeyawo,Rárà,A type of song/elegy
252
+ Àwọn ìkókó yìí kò mọ ọtun yàtọ̀ sí òsì rárá,ÌKÓKÓ,BABY
253
+ Igun ilé ni a kò àdá wa sí,IGUN,CORNER
254
+ Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ fi orin dà wa lára yá,Orin,music
255
+ Òkú tí o kú ni a sin sí itẹ́,Itẹ́,Burial ground
256
+ Ba mi já orín bọ̀ wá ní oko,Orín,chewing stick
257
+ Ogún ti àwọn òbí Tade fi sílẹ̀ fún un titó lo aye,OGÚN,INHERITANCE
258
+ Ẹ̀yin wo lẹ n pariwo níbè yẹn,Ẹ̀yin,Those
259
+ Iṣẹ igbà hìhun ni Ishọ̀la yan láàyò,Igbà,rope use to climb palm tree
260
+ Ọ̀lẹ ni Àlàmú kòlè kọ igba ebè l'oko,Ọ̀le,Lazy
261
+ okó ẹṣin yìí gùn ju àwọn èyí tí ó wà nínú ọgbà lọ,Okó,penis
262
+ Ẹ̀ya ti o wà ní ara rẹ̀ kọ jà ohun ti a lè fẹ nu sọ,Ẹ̀ya,Tears
263
+ Kòsí ohun ti gaga ọwọ̀ kan le se,Gaga,A piece
264
+ Ọ̀kan lára àwọn ìdí náà buru gán,Idì,Eagle
265
+ Igi ìgbá yìí so ní ọdún yìí púpọ̀,Ìgbá,locus
266
+ Ọmọ tí ó jí gègé mi nìyí,JÍ,STEAL
267
+ Kì bá dára kí o sá fún àwọn ọdaju ènìyàn yẹn,SÁ,RUN AWAY
268
+ Ǹjẹ́ kìí se aago mẹ́ta ni ẹ padà fi ìpàdé sí,AGO,CLOCK
269
+ Akin lo járọ́ ti Ṣọla pa fún wa,Járọ́,To expose a lie
270
+ Ohun tí Adé se fún àbúrò rẹ̀ burú gan,Ohun,Thing
271
+ Gbiyanju kí o lọ sí ilé ìwòsan fún iwò ojú,Iwò,spectacle
272
+ iná jó ilé náà,Iná,Fire
273
+ Oyebisi fẹ́ dé ọ̀dọ̀ àyò rẹ̀ lókè odò,ÀYÒ,FAVORITE
274
+ kí olùwà fi ìtọ́ ràn wá lọ́wọ́,Ìtọ́,Guide
275
+ Bàbá ran ọmọ ní ike ní ọjà,Ike,plastic
276
+ Iná ko jẹ ki awọn adiẹ náà gbádùn,Iná,Lice
277
+ Òdo ni Àlàmú gba nínú idanwo to ṣe,Òdo,Zero
278
+ ọ̀fà jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ìlú tí o gbajúgbajà ní ìpínlẹ̀ kúárà,ọ̀fà,city in kwara state
279
+ Ojo rọ̀ ni ọsẹ to kọjá,Ọsẹ,Week
280
+ Adura Bukọ́la gbà nígbà tí wọn fi ire rẹ le lọwọ,Ire,Goodness
281
+ Mo nífẹ̀ẹ́ láti ra Àgò mìíràn fún àwọn adìẹ mi,ÀGÒ,THE MOBILE CAGE FOR CHICKEN
282
+ ỌSÀN tí o wà ní Orí igi náà ti pọ́n,Ọsàn,Orange
283
+ Adukẹ́ gún iyán nínú odó,Odó,Mortal
284
+ Kí ojú máa ríbi gbogbo ara lò gun rẹ̀,Ara,Body
285
+ ìwọ àti èkejì rẹ ẹ Pin ọsán yìí Àbò,Àbò,Half
286
+ Èmi ati ìyàwó fẹ́ lọ sí bi ayẹyẹ ní ọ̀la,Ọ̀la,tomorrow
287
+ Ẹ̀re akọni ọdẹ náà wà ní ẹnu ìloro ìlú wọn,Ère,Statue
288
+ Mo dá arábìnrin náà ni oko owò,Owò,business
289
+ Eku ilé kò ṣe gba ojú bọ̀rọ̀ fún,EKU,RAT
290
+ Ike yìí mọ rẹwà púpọ̀,Ike,plastic
291
+ Mo ṣe àkíyèsí wípé àwọn Àlàmú ma ń ní ìwà púpọ̀,ÀLÀMÚ,A MALE NAME
292
+ Nínú ìjànbá ọkọ̀ to waye gaga irun ori ẹnìkan kò jona,Gaga,A piece
293
+ Dókítà òyìnbó tí gbà á ní ìmọ̀ràn pé kí ó wá gba abẹ́rẹ́ titanọọsi sí ojú egbò rẹ̀ láti dènà aburú ọjọ́ iwájú,EGBÒ,WOUND
294
+ Ẹ bá mi pé ìyá ìkókó pé mo fẹ́ rí i,ÌKÓKÓ,BABY
295
+ Ọgbọ̀n náírà ni mo ra ọsàn ẹyọ̀kan l'ọja,Ọgbọ̀n,Thirty
296
+ ọbẹ̀ ọ́yọ́ máa dùn jẹ́ ẹ̀bà tútù,Ọ́YỌ́,VEGETABLE
297
+ "Ṣọla ati awọn akẹgbẹ tó jọ kò ọ̀wọ́ rin, nígbà tí wọn jáde ile-iwe",Ọ̀wọ́,Group/ Collectively
298
+ Ìsàlẹ̀ ọrọ̀ a máa ní ẹ̀gbín ní ọ̀pọ̀ ìgbà,ỌRỌ̀,WEALTH
299
+ kínni ìdí tí Akin se n sá lọ?,Ìdí,Reason
300
+ Iṣẹ ọsẹ ni ìyá àgbà n ṣe,Ọsẹ,Soap
301
+ Fáṣítì ìjọba àpapọ̀ ti Ilé-Ifè dára púpọ̀,IFẸ̀,A TOWN IN OSUN STATE NIGERIA
302
+ Àwọn Olórò kéde pé orò yóò jáde lọla,ORÒ,A god in Yoruba land
303
+ Ọ̀tunla ni àwọn agbagba ilé yóò pín ogún,OGÚN,INHERITANCE
304
+ ògèdè jẹ ohun tí a gbọ́dọ̀ se kí a tó wọ ìgbàlẹ̀,Ògèdè,incantation
305
+ Gbogbo Abo ni wọ́n ti ni ọkọ tán,Abo,Female
306
+ "Aya ọmọdé ni ìwà àìgbọràn pọ̀ sí, Egba sì ni ó lè le jáde",ẸGBA,CANE
307
+ Àwọn dókítà tí ṣe iṣẹ́ abẹ láti lè kó ọyún inú apá ọkùnrin náà kúrò,ỌYÚN,TUMOR
308
+ Àwọn Kẹ́kẹ́ kò jẹ́ kí a gbádùn igbá tí a gbìn rárá,KẸKẸ,A GRUB WHICH MAKES HOLES IN CALABASH
309
+ Àgò ni yóò dé adìẹ gbẹyin,ÀGÒ,THE MOBILE CAGE FOR CHICKEN
310
+ "IRỌ̀ pípa ni gbogbo ìgbà, kì í jẹ́ kí a nìyí",IRỌ́,LIE
311
+ Mo nílò kí alagbẹdẹ bá mi rọ ẹyá méjì lónìí,ẸYÁ,TEAR
312
+ Ìyà Àṣàkẹ́ kì í jẹ́ ọbẹ̀ ọ́yọ́ rárá,Ọ́YỌ́,VEGETABLE
313
+ Bàbá Abiodun abà arẹ̀sà kúndùn Ìfà púpọ̀,ÌFÀ,FREEBIE
314
+ Èrè ti Ṣọla jẹ lórí ọjà rẹ̀ lo fi ra asọ ọdún,Èrè,Gain/Profit
315
+ ìwọ ni o se iku pa ọmọ náà,Ìwọ,You:
316
+ Akin se àbúrò rẹ ni osẹ́,Ọsẹ́,injury
317
+ Àwọn Obí n ṣeré ní àyíká,Obí,kid/baby
318
+ Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ náà bẹ̀rẹ̀ láti kí Ọ̀gá wọn,BẸ̀RẸ̀,BEND
319
+ Aró dà sí asọ tuntun ti mo ṣẹṣẹ rà,Aró,Dye
320
+ Ṣọla ati Bode nlọ ọjà lọla,Ọjà,market
321
+ Ẹsẹ̀ ni ọta ti ba ọdaràn náà,Ọta,Bullet
322
+ Ìgbá ti mọ ká ní àná ni mo fí ṣe irú to wa nínú ọbẹ̀ yìí,Ìgbá,locus
323
+ Ọwọ́ ni olukọ ti fún ọmọ náà lẹ́gba,Ọwọ́,Hand
324
+ Ìyá àgbà so wípé àsán ni a máa jẹ oúnjẹ alẹ́,ÀSÁN,EATING FOOD WITHOUT ADDING FISH/MEAT
325
+ Ogunleke ń gbìyànjú láti pá àsá abàmì náà,ÀSÁ,EAGLE
326
+ "ìyàwó burúkú dùn-ún fẹ́, àna burúkú ni o dùn-ún ni",Àna,inlaw
327
+ Bá mi dá Ẹ̀kọ wá ní búkà,Ẹ̀kọ,Local food derived from maize
328
+ Ẹ̀kọ̀ ni ọkùnrin kọ Obìnrin nílé ọkọ,Ẹ̀KỌ̀,Abandoned
329
+ Oyè jagun nílu Feyikogbon da wàhálà silẹ,Jagun,A military title
330
+ OLÓRÍ ilé àwọn Talabi ti tẹri gba aṣọ,OLÓRÍ,LEADER
331
+ Ìyá mi àti orogún wọn nífẹ̀ẹ́ ara wọn dọba,OROGÚN,RIVAL
332
+ Ríru omi ÒKUN bo ọkò ojú omi náà mọlẹ,Òkun,Ocean
333
+ itẹ́ ni wọ́n sin àwọn òkú ṣí,Itẹ́,Burial ground
334
+ Yíyọ́ Ẹkùn t'ojo kọ́ o dábírà ni,Ẹkùn,Leopard
335
+ Bí àgbẹ̀ bá da oko dáadáa yíò rí èrè níbẹ̀,Oko,farm
336
+ Ẹ̀kún rọ́bà epo ni mo fẹ́,Ẹ̀kún,Fullness
337
+ ORÍ ni kí ẹ ma bọ kí ẹ fi òrìsà sílẹ̀,ORÍ,
338
+ Ọ̀tunla ni ọdún Ògún ni ìlú Ondo,ÒGÚN,god OF THUNDER
339
+ Olóyè Ọ̀yọ́ Aláàfin ni bàbá mi,Ọ̀YỌ́,A STATE IN NIGERIA
340
+ Ọdẹ fí ỌFÀ pa ọ̀kẹ́rẹ́ ni orí igi,Ọfà,catapult
341
+ Ọgbọ́n ọlọgbọ́n ni kìí jẹ kí a pè àgbà ní wéré,Ọgbọ́n,Wisdom
342
+ "Ṣe ọmọ náà wá sí ilé ìwé,rárá kò wá",Rárá,At all
343
+ àyà Ṣọla já nígbà tí o gburó ìbọn,Àyà,Chest
344
+ ìlú òkò jẹ́ ọ̀kan lára ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́,Òkò,A town in Oyo state
345
+ Òkùn kọni kùn ki onínú má monú,Òkùn,Darkness
346
+ Gẹ̀gẹ̀ ti Aduke ni mú kí o burẹ́wà,Gẹ̀gẹ̀,A protuberance on the neck
347
+ Àwọn ilé tí o wà ní Àjá ti wọ́n jù,Àjá,A place in Lagos
348
+ Apá kan ni ọkùnrin náà ni,Apá,Hand
349
+ Ọjọ́ ìsinmi tó ń bọ̀ ni ìsìn ìkẹyìn nínú oṣù yii,ÌSÌN,WORSHIP
350
+ Ìpínlẹ̀ Ògùn náà rẹ̀wá ni ìwọ̀nba,ÒGÙN,A STATE IN NIGERIA
351
+ Àwọn ìjọba tí ṣe àdéhùn láti san owó òógùn ojú àwọn òṣìṣẹ́,ÒÓGÙN,SWEAT
352
+ "Pakute tí mo dẹ fún ọ̀ọ́fàn, aláàmù ló mú",ALÁÀMÙ,LIZARD
353
+ "Àjọ àkọ́kọ́ tí mo dá, ní mo fi ra kẹ̀kẹ́",ÀJỌ,CONTRIBUTION
354
+ Mo fẹ́ kí a yọ sí ọ̀daràn náà ni òjijì,ÒJIJÌ,SUDDENLY
355
+ Ọ̀wẹ̀ tí mo gbà ní ọdún tí ó kọjá pé mi púpọ̀,Ọ̀wè,A COMPANY SUMMONED TO ASSIST ONE OF THEIR MEMBER IN MANUAL LABOR
356
+ ikùn aláboyún naa tóbi púpọ̀,Ikùn,Stomach
357
+ Oṣù tí ó ń bọ̀ ni ìyá Ayinla máa jáde nílé opó,OPÓ,WIDOW/WIDOWER
358
+ ẹni tí ò ki ni kú ilé ó pà dànù ẹku Abọ̀,Abọ̀,welcome
359
+ Igi ọ̀pẹ ẹgbẹ̀rún kan ni a gbìn sí orí ilẹ̀ tuntun náà,Ọ̀PẸ,PALM
360
+ Ẹ̀KỌ́ ni àwọn akẹ́kọ̀ọ́ lọ kọ́ ní ogbà àwọn ẹranko,Ẹ̀KỌ́,Knowledge
361
+ Ògùn yìí dára fún ojú ṣíṣú,ÒGÙN,MEDICINE
362
+ Aràrá ni olùkọ́ ède yorùbá,Ràrá,Dwarf
363
+ Ó yẹ kí gbogbo sa ipá láti dènà aburú ọjọ́ iwájú,IPÁ,ABILITY
364
+ Òpó náà kò rí Ẹsẹ̀ fi múlẹ̀ dáradára mọ oooo,ÒPÓ,PILLAR
365
+ "Ọmọ bíbí ìlú ìré ni Akinyemi, ọ̀rẹ́ Taiwo",Ìré,"A town in Osun State, Nigeria"
366
+ Ẹ gbìyànjú láti fi ilẹkun ilé sí pí padé,PADÉ,"TO SHUT, TO CLOSE UP"
367
+ Ọsẹ dúdú ni Adé fi n wẹ̀,Ọsẹ,Soap
368
+ Igi Afàrà dára fún ilé kíkàn,Afàrà,Shingle wood
369
+ Mo nílò láti kó àwo bí mẹ́ta lọ sí ilé ẹ̀kọ́,ÀWO,PLATE
370
+ Osé mẹta ni ó wà ní ilẹ̀ fún nílò ní ọdún yii,OSÉ,A TOOL USED BY SANGO WORSHIPPERS
371
+ Ọmọ náà gbá iná mú,Iná,Fire🔥
372
+ Ẹ Funmi ni ìṣù ọkà mẹ́jọ péré,ỌKÀ,YORÙBÁ LOCAL FOOD
373
+ Bàbá Orisabunmi pa ejò isán ní ńlá kan ní ọ̀sẹ̀ tó kọjá,ISÁN,A TYPE OF SNAKE (WHICH LIKE SLEEPING)
374
+ "Àáyá gbọ́n, Ògúngbè gbọ́n",Àáyá,species of monkey
375
+ "Ní òjijì, òkúta ńlá ré lu ọdẹ náà",ÒJIJÌ,SUDDENLY
376
+ Mo fi agbọ̀n kó irè oko wá lé,Agbọ̀n,Basket
377
+ "ijọ́ tí ènìyàn bá dá ẹ̀jẹ́ kìí mọ̀, àyàfi tí ìṣòro bade",Ẹ̀jẹ́,convenant
378
+ "Ajá tí yóò sọnù, kìí gbó ìfé ọdẹ",ÌFÉ,WHISTLING
379
+ Ẹ rí i dájú pé Irọ̀ ni àwọn ọmọ tí ẹ fẹ́ kó jọ fún ìdíje yìí,IRỌ̀,AGE MATE
380
+ Itan mi ti ó tóbi ni kò jẹ́ kí n le sáré dáadáa,ITAN,THIGH
381
+ kò dára kí ọmọdé máa wo òjìji ara rẹ̀,ÒJÌJI,SHADOW
382
+ Ìlù àti orin jẹ́ ọmọ ìyá kan náà,Ìlù,drum
383
+ Agbè bàbá Kọ́lá elẹ́mu tí kún fún ẹmu gidi,AGBÈ,"BIG GOURD, NORMALLY USED BY PALM WINE TAPPER"
384
+ Ẹ kìlọ̀ fún àwọn ọmọ yín kí wọn má fi Ògún búra èké o,ÒGÚN,god OF THUNDER
385
+ "A n t'ori Àjà jà,Àjà ní ta lọ njà lẹ́kùnlé òhun",Àjà,Roof
386
+ Ìsín ni Ìwọ̀ mi gbé wa si òkè odò,ÌSÍN,SMALL CATFISH
387
+ "Kí á má parọ́, Ìfà ni ó kó bá Fioye",ÌFÀ,FREEBIE
388
+ ỌSÁN tí ó di ìlù náà mu' jẹ́ kí ohùn dún dáadáa,Ọsán,One of the rope used to tie talking drum
389
+ Àró pa ẹran ìgbẹ́ bọ̀ l'oko,Àró,Name of person
390
+ Adìẹ ìyá àgbà ti n yé ẹyin,Ẹyin,Egg
391
+ "Ibi tí Ìfẹ́ bá wà, ohun gbogbo tí ó dára ni yóò wà níbẹ̀",ÌFẸ́,LOVE
392
+ Orílèdè náà ní lò Àbò púpọ̀,Àbò,Security
393
+ "Ọdẹ tí yóò pa ẹkùn, kò múra dáadáa ní o",ỌDẸ,HUNTER
394
+ Ilé-iṣẹ́ nla kan tun ti bẹrẹ iṣẹ ni ìlú Ọ̀tà,Ọ̀tà,"A town in Ogun State, Nigeria"
395
+ Ìlú Adà dára fún ọmọlúwàbí láti gbé,ADÀ,"A TOWN IN OSUN STATE, NIGERIA"
396
+ Mo fẹ́ sáré de Abẹ́ igi láti lọ ta ayò,AYÒ,GAME
397
+ Bá mi mu ìtẹ̀ wá nínú ilé,Ìtẹ́,Mat
398
+ òkò àjẹ́ ò ní bà ẹ́ tìẹ ni yíò ba àjẹ́,Òkò,stone🪨
399
+ Àwọn Ràrá wa sí orí ìtàgé fún eré àdídùn,Ràrá,Dwarf
400
+ igi Ọ̀mọ̀ wúlò púpọ̀ fún lílò,Ọ̀mọ̀,Tree of the banyan family
401
+ Mo nílò orógùn mẹta kún méje tí a rà ni ijẹta,ORÓGÙN,"TURNING STICK, TURNER"
402
+ Ayọ̀ ni orúkọ ọmọ náà,Ayọ̀,Joy
403
+ Okùn kìí gùn ko ma ní ibi tí o ti wá,Okùn,Rope
404
+ Ohùn ẹkún ọmọ náà ni mo gbọ́ tí mo fi jáde síta,Ohùn,Sound
405
+ Ọjọ ayọ̀ ni ọjọ ti mo jade ni ile-iwe gíga,Ayọ̀,Joy
406
+ Ọmọ náà pọ́n bi ọ̀lẹ̀,Ọ̀lẹ̀,Local food derived from beans(moimoi)
407
+ "Ìkokò wọlu, èèmò dé, ọ̀rọ̀ di b'òlọ yà fún mi",ÌKOKÒ,HYENA
408
+ Ogún maàkì ni ẹni kọ̀ọ̀kan yín gbọdọ̀ gbà,OGÚN,TWENTY
409
+ Igbìyànjú mi láti la ipa rere nínú ayé yìí kò ní já sí asán,IPA,PATH
410
+ Solape n fi gégé ìyá náà bú u,Gẹ̀gẹ̀,A protuberance on the neck
411
+ Àwọn esú jà nínú oko ọ̀rẹ́ mi ni ọdún tí ó kọjá,ESÚ,LOCUST
412
+ Ọmọ náà fi orí jálé agbọ́n,Agbọ́n,wasp
413
+ Ewé igi náà járọ̀ sára òwú alantakun,Járọ̀,To break a fall
414
+ Bàbá Folake sọ wípé ègbo ni òun fẹ́ jẹ,ÈGBO,FOOD DERIVED FROM MAIZE
415
+ "Ẹ̀yin tí ẹ joko sibẹ̀ yẹn, ẹ fura o",Ẹ̀yin,Those
416
+ Àyà ni bọọlu ti bá agbabọ́ọ̀lù náà,Àyà,Chest
417
+ Mo fẹràn láti máà ṣọ èdè gẹ̀ẹ́sì,Èdè,Language
418
+ Ìwé yìí kò rọrùn ni kíkà,ÌWÉ,BOOK
419
+ Ẹ ní láti ṣètò bí a ó ṣe pàdé lọla,PÀDÉ,TO COME TOGETHER
420
+ ikún jẹ ọgẹdẹ ikún n rèdí,Ikún,A kind of Squirrel
421
+ Àwọn òní agbe náà nínú ọrẹ,ỌRẸ,ALMS
422
+ "Orí igún kò ṣàdédé pá, ó ní ìtàn tó rọ̀ mọ",IGÚN,VULTURE
423
+ Ìkòkò mẹwa ló fọ níbi ìjàmbá tó ṣẹlẹ̀ lọ́nà irẹsa,ÌKÒKÒ,CLAY RESERVOIR
424
+ Adùn gé irun rẹ nitori iná orí,Iná,Lice
425
+ Ọlè wà nínú ọ̀kẹ́rẹ́ ti bàbá ọdẹ pa,Ọlẹ̀,Foetus
426
+ Wọn fi ọ̀daràn náà ṣe ẹ̀ṣín ni ojúde ọba,Ẹ̀SÍN,SHAME
427
+ Mo nílò ikàn méjì péré láti fi jẹ isu mi,IKÀN,GARDEN EGG
428
+ Mo ra asọ ní ojà laisan owó,Owó,money
429
+ Ọmọ náà sun yàrá ìyá rẹ̀ nigbati o fi ìsáná seré,Sun,To burn
430
+ Igbá tí mo fí pọn omi já sí odò lànàá,Igbá,fetcher
431
+ Olúwa bun àwọn ọkọ àti aya ní Obí tuntun,Obí,kid/baby
432
+ Ìlú Ọ̀lá ko ju mẹ́ẹ̀lì meji lo sí ìlú Ejigbo,Ọ̀LÀ,a town in Osun State
433
+ Erè wọ́ ewúrẹ́ náà mì,Erè,Snake (python)
434
+ Òdo ni ọ bẹrẹ nọ́ḿbà ẹ̀rọ aláàgbéká ti Tolu ń lo,Òdo,Zero
435
+ Kílódé tí ọ̀rọ̀ òdì jáde lẹnu rẹ,Òdì,other side of something
436
+ inú yàrá mi kò ní àyè tí ó tẹ́mi lọ́rùn rárá,ÀYÈ,SPACE
437
+ Igbó mímu ti fẹ́ yí ọmọ náà lórí,Igbó,India helm
438
+ Àwọn ikán tí ba gbogbo igi náà jé,IKÁN,TERMITE
439
+ Mo fẹràn láti máà jẹ Edé púpọ̀,Edé,Crayfish
440
+ Ìlú Ọ̀wọ̀ jé òkan lára àwon ìlú to tóbi jùlọ ní ìpínlè Ondó,Ọ̀wọ̀,A town in Ondo State
441
+ Ọ̀lẹ̀ ati ẹ̀kọ ni Ṣọla jẹ l'ọsan,Ọ̀lẹ̀,Local food derived from beans(moimoi)
442
+ Okùn agba ni bàbá fi di iṣu náà wálé,AGBA,A TYPE OF ROPE FOUND IN FOREST
443
+ Dókítà isegun oyinbo ti o da ìwọ́ ọmọ náà mọ iṣẹ dojú àmì,Ìwọ́,Umbilical cord
444
+ Adewale alapata nílò láti pọ́n ọ̀bẹ rẹ̀ dáadáa,Ọ̀BẸ,KNIFE
445
+ Ǹjẹ́ ìwọ ti jẹ Awújẹ rí bí?,AWÚJẸ,A TYPE OF PLANT RESEMBLE BEANS
446
+ "Taye ati Kehinde ko ga ju ara wọn lọ, ọgba láwọn méjèjì",Ọgba,Equal
447
+ Ṣé o fẹràn bàtà tí bàbá mi rà lànàá,Irú,type
448
+ Asọ àrán ni Ade wo jáde l'ana,Àrán,cloth
449
+ Kínní ipá tí ó sà lórí gbogbo àwọn akẹ́kọ̀ọ́ rẹ?,IPÁ,ABILITY
450
+ Olóyè Àró n jẹ́jọ́ ni ààfin ọba,Àró,Name of person
451
+ Àwọn ẹyẹ tí fẹ́rẹ̀ jẹ gbogbo ọkà oko baami tán,ỌKÀ,GUINEA CORN
452
+ Mo ra Edé ní ọjà láti fi se ọbè,Edé,Crayfish
453
+ Kẹkẹ tí ba gbogbo igba oko Solape jẹ́,KẸKẸ,A GRUB WHICH MAKES HOLES IN CALABASH
454
+ Ògédé àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ní afẹ kí ó joko níbi ayẹyẹ yìí,Ògédé,Only
455
+ Nínú gbogbo ẹ̀yà tí o wà ní orílẹ̀-èdè àgbáyé ẹ̀yà Yorùbá ló dára jù,Ẹ̀YÀ,Tribe
456
+ Ilẹ̀ ti mọ kọ fún nnkan ọ̀gbìn ní ọdún yìí tó igba,Igba,two hundred
457
+ Ẹja òjìjí ṣòro láti pa púpọ̀,ÒJÌJÍ,A LOCAL NAME OF A FISH
458
+ Mo bẹ Elédùmarè kí ó ṣe mí ní olú ni orile-ede mi,OLÚ,SUPERIOR
459
+ ìgbà àti àkókò kò dúró dé ẹnìkankan,Ìgbà,Time
460
+ Àgbá òfìfo ni ó má ń pariwo,ÀGBÁ,BARREL
461
+ ìdí nì olukọ ti na Ade ni ẹgba,Ìdí,Bottom
462
+ Tẹ́tẹ́ títa tí padà gba aṣọ ni ara Ibikunle,TẸ́TẸ́,GAMBLING
463
+ Jẹ́jẹ́ lọmọ náà joko ki Ṣọla tó dọ́dọ̀ rẹ̀,Jẹ́jẹ́,Gently
464
+ Mọ wọ bàtà sí ẹsẹ̀ rẹ kí o tó jáde,Ẹsẹ̀,leg
465
+ Ẹ sọ́ra níbi fífi ògùn orí fífọ́ wo inú rírun,ÒGÙN,MEDICINE
466
+ Ǹjẹ́ mo le rí ọbẹ̀ ẹgusi díẹ̀,ỌBẸ̀,SOUP
467
+ Àdùnní gbin ewebẹ sínú ọgbà,Ọgbà,Garden
468
+ Ọ̀mọ pọ̀ láàrín ìlú láti lò,Ọ̀mọ,A builder of wall
469
+ Akitiyan olùkọ́ Adé láti rí pé ó ṣe àṣeyọrí lo padà jásí asán,ASÁN,VAIN
470
+ Ọmọ olorì àgbà ní ààfin yìí ni Adekola,OLORÌ,QUEEN
471
+ Gbogbo ìwé bàbá (D O Fagunwa) ni olùkọ́ wa sọ pé kí á rà,ÌWÉ,BOOK
472
+ Ìsìn àná dùn momi púpọ̀ gan-an,ÌSÌN,WORSHIP
473
+ Ìjọba fi rọ̀gùnrọ́gún owó sí ilé ìwé àwọn odi,Odi,dump
474
+ Mo sún fún ọ̀rẹ́ mi nítorí ìwà rẹ̀,Sún,Shift
475
+ Kò sí ohùn tí ènìyàn kò le fi àrà dá,Àrà,unique (wonder)
476
+ Ọbẹ̀ ilá ní ìyá àgbà se fún bàbá l'ana,Ilá,Okro
477
+ "Tí o bá ti jí, dákun gbìyànjú láti jí mi",JÍ,AWAKE
478
+ "Apá ọ̀tún ni ilé mi wà, ní agbègbè ojuelegba",Apá,Hand
479
+ Mo féràn láti máa fi ẹ̀fọ́ tẹ̀tẹ̀ jẹ́ ẹ̀kọ,TẸ̀TẸ̀,A VARIETY OF VEGETABLE
480
+ Jẹ́jẹ́ ni òjò to rọ lana rọ̀,Jẹ́jẹ́,Gently
481
+ "Èmi pẹ̀lú olùkọ́ èdè Yorùbá, awo ni wá",AWO,SECRET
482
+ Irú bàtà wo ní o fẹ́ rà ní ọjà,Irú,type
483
+ ẸYÁ tí Ẹ̀gbọ́n mi fi ń dá ẹmu tí sọnù,ẸYÁ,TEAR
484
+ Mo ra bàtà ní ọjà lánàá,Bàtà,Shoe
485
+ "ORÍ lẹja fí n labú,ORÍ ni akàn n fí lalẹ lódò",ORÍ,
486
+ Àṣà Yorùbá wuyì púpọ̀ láwùjọ àwọn àṣà tí ó kù,ÀṢÀ,CULTURE
487
+ Ọsẹ akọkọ ni oṣù keji odun yii ni ọjọ ìbí mi,Ọsẹ,Week
488
+ Ọmọdé gbọdọ b'ọ̀wọ̀ fún ẹni tó jùú lọ,Ọ̀wọ̀,honour
489
+ Pakute bàbá ọdẹ tí pa ọ̀yà,Ọ̀YÀ,GRASS CUTTER
490
+ "Mo fẹràn ọkọ mi púpọ̀,mi o le fi ọ̀rọ̀ rẹ̀ seré",Ọkọ,husband
491
+ Òjìji Olatunde ń dẹru bàá,ÒJÌJI,SHADOW
492
+ Owó ti a ná níbi ìgbéyàwó náà kò kéré,Owó,money
493
+ Kòsí ẹni tí ọ mọ bi ọlẹ̀ se n dénú alaboyun,Ọlẹ̀,Foetus
494
+ Ìfé ni a fi wa ara wa rí nínú igbó Olugbade,ÌFÉ,WHISTLING
495
+ Oyebisi kò fi ìyè sí ohun tí olùkọ́ rẹ̀ ń kọ́ ọ,IYÈ,MIND
496
+ Ìlú Òró ni a ti ní ṣíṣe lọla,ÒRÓ,"A CITY IN KWARA STATE, NIGERIA"
497
+ Kúnlè sọ ọ̀rẹ́ rẹ̀ ní ìgbò ni imú ni ẹ̀jẹ̀ bá yọ ni imu rẹ̀,Ìgbò,headbutt
498
+ "Bámi rántí sọ fún ìyá Dosumu pé, mo nílò àdá méjì",ÀDÁ,CUTLASS
499
+ ògun aràn tun ti gb'owo lori,Aràn,worm
500
+ Ọdẹ náà pa ERÈ l'oko,Erè,Snake (python)
501
+ Igbó ti kún bo ile baba àgbà,Igbó,Bush
502
+ ẸTÙ méjì ni a ní nílé tí a ń sìn,ẸTÙ,GUINEA FOWL
503
+ Ìwọ́ we mọ ọmọ náà lọrùn nigbati ìyá rẹ̀ bí I,Ìwọ́,Umbilical cord
504
+ Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ lọ sí ilé olùkọ́ lati pọn omi sùgbọ́n wọn ò mú igbá lọ́wọ́,Igbá,fetcher
505
+ Ri dájú pé o ra ògùn fún ikun tí o mu ọ,Ikun,Mucus
506
+ Ilà kẹkẹ dára ní ẹ̀kẹ́ Yéwándé gidigidi,KẸ́KẸ́,A PECULIAR FACIAL MARK
507
+ Olukọ ní kí ọmọ ile-iwe kọọkan mu ọwọ̀ kọọkan wa,Ọwọ̀,Broom
508
+ Awọn ọmọ ogun oril'ede yìí ṣetán láti bá àwọn agbesunmomi jagun,Jagun,To make war
509
+ "Taani òye ayé yìí yé, kí ó wá sọ",AYÉ,EARTH
510
+ ìyá ra bàtà tuntun fún ọmọ rẹ̀,Bàtà,Shoe
511
+ Ọwọ́ àwọn agbofinró tẹ ọkùnrin tó n ta igbó,Igbó,India helm
512
+ "Pátákò Ẹfọ̀n, kakaka lo má ń ta ajá lẹ́nu",PÁTÁKÒ,HOOF
513
+ Àwọn Ikán yìí nílò àmójútó gidigidi,IKÁN,TERMITE
514
+ Ọbẹ̀ ilá pẹlú gbegiri a máa dùn lórí amala,Ilá,Okro
515
+ Ní bo ìyá ìkókó gbà lọ,ÌKÓKÓ,BABY
516
+ Ìná àpà ni Kúnlè ná fún olorin,Ìná,spent
517
+ Ìlú Adà ni ìyá Rọlakẹ ti bẹ̀rẹ̀ ìgbésí ayé rẹ̀,ADÀ,"A TOWN IN OSUN STATE, NIGERIA"
518
+ Bàbá mí ra ọkọ̀ ayọ́kẹ́lẹ́ ní àná,Ọkọ̀,CAR
519
+ Ó ní láti gbọ́n epo ra ojú Ówo náà kí ó lè tètè dẹ̀,ÓWO,BOIL
520
+ Ọ̀gà inú ayanran mi ti sá lọ,Ọ̀GÀ,CHAMELEON
521
+ Ọ̀dẹ̀ ni gbogbo wa yóò jókòó sí lónìí,Ọ̀DẸ̀,PASSAGE
522
+ Solape ń gbìyànjú láti gba ilé-ìtajà sí bẹrẹ,BẸRẸ,"AN AREA IN IBADAN, OYO STATE"
523
+ Ma se sọ ọ̀rọ̀ òdì sí ọmọ ẹní Kejì rẹ,Òdì,other side of something
524
+ Ọmọ náà jẹun sí ikùn tí o sì yó,Ikùn,Stomach
525
+ Bàbá Atinukẹ ní oko ńlá mẹ́ta tí ó fi gbin ikàn,IKÀN,GARDEN EGG
526
+ Ìgbò ni Ṣọla fi má n bori awọn alátakọ̀ rẹ̀ nígbà tí ìjà bá wáyé-,Ìgbò,headbutt
527
+ "Ti igbó ba pọ̀ ní àyíká, o le ṣe òkùnfà ẹ̀fọn",Igbó,Bush
528
+ Awò ni àwọn dókítà fún Olabisi tí sọnù,AWÒ,SPECTACLE
529
+ Iyè ọmọ náà ti ra pẹ̀lú ibẹru,IYÈ,MIND
530
+ lọ ká ìtẹ́ tí o fi sún,Ìtẹ́,Mat
531
+ Bí a múra sí iṣẹ ọwọ ẹni oseese kìí ìṣẹ́ jìnà sí ni,Ìṣẹ́,poverty
532
+ Iwe adìẹ náà kún mi lẹ́nu púpọ̀,IWE,GIZZARD
533
+ Ọgbọ̀n ọjọ́ ni o wà nínú osù kẹrin,Ọgbọ̀n,Thirty
534
+ "Àsá tí ó gbémi ni adìẹ, kò ní pẹ́ bá ọlọ́jọ́ pàdé",ÀSÁ,EAGLE
535
+ Ìlà ti adari ayo fa silẹ ni agbaboolu naa fi'binu parẹ́ ti o fi gba kaadi pupa,Ìlà,line
536
+ Ìkòkò ìyá àgbà tí fọ́ yángá-yángá,ÌKÒKÒ,LOCAL POT
537
+ Ọmọ bíbí ìlú Ọ̀wọ̀ ni Gomina ipinlẹ Òndó àná,Ọ̀wọ̀,A town in Ondo State
538
+ Olùkọ́ àgbà fún àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ní owó láti fi ra oúnjẹ,Owó,money
539
+ jagunjagun náà fí ọ̀kọ̀ gba ara rẹ̀ lẹ ní ojú Ogun,Ọ̀kọ̀,spare
540
+ Ìlú Awó kò jìnnà sí ìlú Gómìnà,AWÓ,A TOWN IN OSUN STATE NIGERIA
541
+ Ègbo díẹ̀ àti ẹ̀wà díẹ̀ ti tó fún un èmi,ÈGBO,FOOD DERIVED FROM MAIZE
542
+ Ogun jalumi kìí se tí ènìyàn lè gbàgbé,OGUN,WAR
543
+ "Lẹ́yìn tí a fi ẹ̀fọ́ tẹ̀tẹ̀ jẹ iyán tán, bàbá àgbá pa aalọ fún un wa",TẸ̀TẸ̀,A VARIETY OF VEGETABLE
544
+ Pátákó ajúwe lo jẹ́ atọ́na láti dé ilé ìjọsìn naa,PÁTÁKÓ,"PLANT, BOARD"
545
+ Owó àjọ máa ń bo ènìyàn ní àṣírí púpọ̀,ÀJỌ,CONTRIBUTION
546
+ "Fọlákẹ́ fi ogún ẹgbẹ̀rún s'owo, o sí jẹ èrè ẹgb��run máàrún",Èrè,Gain/Profit
547
+ Ìsín ni ó pọ̀ jù ni odò adágún inú oko mi,ÌSÍN,SMALL CATFISH
548
+ Eré ni Ṣọla ati Dayọ nṣe ki o tó d'ija,Eré,Play/Drama
549
+ Ishola rí owó ribiribi níbi ọkà oko rẹ̀ ni ọdún yìí,ỌKÀ,GUINEA CORN
550
+ Ohun amohunmaworan rẹ ni lọ sókè ju,Ohùn,Sound
551
+ Àwọn ẹlẹ́sìn ìbílẹ̀ yóò yọjú sì Kábíyèsí ní òṣùpá mẹta tó ń bọ̀,Ẹ̀SÌN,RELIGION
552
+ Ọmọ náà ni ọ̀wọ́ lẹyìn,Ọ̀wọ́,Group/ Collectively
553
+ eegún tí yóò erin kò sí nígbó,Eegún,masqurade
554
+ Bí ajá bá rí olówó Re yíò ju ìrù sí,Ìrù,tail
555
+ Awọn olè se ọkùnrin naa ni osẹ́ púpọ̀,Ọsẹ́,injury
556
+ Irọ̀ ni èmi àti Adeyọde,IRỌ̀,AGE MATE
557
+ "Àgbà kì í wà lọ́jà, kí orí ọmọ tuntun kó wọ́",ÀGBÀ,ELDERLY PERSON
558
+ wakati meji ni ọkọ ayọkẹlẹ yóò lo lọnà láti ìlú ìlá sí ìlú Osogbo,Ìlá,a town in Osun state
559
+ Ará kannáà ni ìran ìbíní àti yorùbá jẹ́,Ará,related people
560
+ Orí òró ni àwọn òní janduku pa ọkùnrin náà sí,ÒRÓ,STAND
561
+ ìyàwó tí ọkọ fẹràn jù lo ń se ọbẹ̀ fún ọkọ,Ọkọ,husband
562
+ Ìlú Ìbàdàn ni àwọn akẹ́kọ̀ọ́ lọ ní òpin ọ̀sẹ̀,Ìlú,Village
563
+ "Bí obìnrin bá fi ojú di orò, yóò dá ara rẹ̀ ni ẹ̀bi",ORÒ,A god in Yoruba land