audio
audioduration (s)
1
5.59
text
stringlengths
2
59
A kì í ṣe oníṣòwò
A kọ́kọ́ jẹun ká tó lọ
A lọ kàwé
A máa ṣiṣẹ́ lọ́la
A ń ṣiṣẹ́ nígbà náà
A ní mọ́tò
A ò burú
A ò máa ń gbá bọ́ọ̀lù láàlẹ́
A ò mọ bí a ṣe ń ṣe
A ò rẹ́rìn
A ṣe oúnjẹ láì ní ìyọ̀
A wà ní ilé
Àga wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ tábìlì
Aago mélòó ló lu
Apá mi ń dùn mi
Àwa kò lọ béèrè
Àwa la jẹ
Àwa la sáré
Àwa lọ rí bàbá wa
Àwọn bàtà yìí
Àwọn ilé yẹn
Àwọn kò ní olóǹgbọ́n
Bá mi kọ̀wé
Bàbá náà ni kí n rà ẹ̀wẹ̀
Bàtà wà lábé ibùsùn
Bàtà wà níbẹ̀
Báwo ló máa ṣe ṣe ìdánwò náà
Báwo ló ṣe fẹ́
Báwo ló ṣe lè ṣiṣẹ́
Báwo ló ṣe mọ Dáfídì
Báwo ló ṣe rí mọ́tò
Báwo ni mo máa ṣe lọ sí ọjà
Báwo ni wọ́n ṣe rí owó
Dáfídì bẹ̀ mí pé kí n má bínú
Dáfídì kò lọ wá
Dáfídì kò ní olùkọ́
Ẹ dín owó síi
Ẹ jọ̀ọ́ jẹ́ kí n wòlé
Ẹ kì í ṣe olórin
Ẹ ò jẹ́ olórin
Ẹ̀káàsán
Ẹ kú rọ̀lẹ́
Èló ni bàtà yìí
Èmi kò ní olùkọ́
Èmi ń jẹun
Ẹran wà níbẹ̀
Ẹ̀wò ló fẹ́
Ẹ̀wò ni wọ́n rà
Èyí ni ìdí tí mo fi lọ
Ẹ̀yìn
Ẹ̀yìn kì í kọ́rin
Ẹ̀yìn kò ní olórin
Fún ìtàn ọjọ́ ẹbí
Gídígbọ̀
Ìdákẹ́jẹ́
Ìforúkọsílẹ̀
Ìjọ́sìn yìí mú inú mi dùn
Inú mi bàjẹ́
Inú mi ń dùn mi
Inú rẹ̀ bàjẹ́
Ìrìnàjò náà dùn mọ́ mi gan-an
Ìrìnàjò náà dùn mọ́ mi nínú
Ìwọ tàbí èmi
James fẹ́ kí n má lọ
Jẹun síi
Jọ̀wọ́ kọ́ mi bí a ṣe
Ká tó sọ̀rọ̀
Kí a tó sọ̀rọ̀
Kí ni ìdí tí a fi rà mọ́tò
Kí ni ìdí tí a rà mọ́tò
Kí ni ìdí tí o fẹ́ lọ
Kò mọ bí a ṣe ń kọ́rin
Kò rẹ́rìn
Kò sí níbí
Kò tíì sètán
Lẹ́yìn tí mo jẹun mo lọ sùn
Lọ
Lójoojúmọ́
Má jẹ́ kí o jẹun
Má jẹ́ kó sùn
Mi kì í jẹ́ ẹ̀wà
Mi kì í lọ jẹun
Mi ò fẹ́ kó lọ
Mi ò jẹ́ olùkọ́
Mi ò rántí bóyá o jẹun
Mi ò rẹ́rìn
Mo fẹ́ kọ́ ẹ̀kọ́ láti di dókítà
Mo fẹ́ lọ ṣùgbọ́n mi ò ní owó
Mo gbọ́ pé o fẹ́ràn rẹ
Mo jẹ́ ọmọ ọdún méjìlá
Mo jókòó láàárín wọ́n
Mo lọ rà aṣọ
Mo máa jáde
Mo máa ṣiṣẹ́ láàlẹ́
Mo mọ bí o ṣe lè ṣe
Mo mọ bí wọ́n ṣe ṣe
Mo ń jẹun báyìí
Mo ní láti
Mo ní láti rà ilé
Mo ṣe gẹ́gẹ́ bí àṣẹ rẹ