file_name,transcription wavs/yorubatts_00000.wav,"Jọ̀ọ́, dòmi" wavs/yorubatts_00001.wav,Mo ní ko kawé wavs/yorubatts_00002.wav,Ẹ̀ ti jẹun wavs/yorubatts_00003.wav,Wọ́n ṣiṣẹ́ gidigidi wavs/yorubatts_00004.wav,Ó máa ń jẹun ní òwúrọ̀. wavs/yorubatts_00005.wav,Awon iwé yẹn wavs/yorubatts_00006.wav,ìtàn wavs/yorubatts_00007.wav,Ó ń sùn nígbà tí mo de wavs/yorubatts_00008.wav,Èló ni bàtà naa? wavs/yorubatts_00009.wav,Ó yẹ kẹ yára lọ wavs/yorubatts_00010.wav,Óun ni wavs/yorubatts_00011.wav,Oun kọ́ ni olùkó wavs/yorubatts_00012.wav,gẹ́gẹ́ bó ti wù ú wavs/yorubatts_00013.wav,A máa ṣiṣẹ́ lọ́la wavs/yorubatts_00014.wav,Ilé rẹ wavs/yorubatts_00015.wav,Mo máa ń rerin nigbagbogbo wavs/yorubatts_00016.wav,bóyá wavs/yorubatts_00017.wav,àti wavs/yorubatts_00018.wav,Ilé ńlá wavs/yorubatts_00019.wav,Mo fẹ́ kòkò sinmi wavs/yorubatts_00020.wav,Ó ra kẹ̀kẹ́ látí máa gùn lọ sí ilé ẹ̀kọ́ wavs/yorubatts_00021.wav,Wọ́n ti lọ wavs/yorubatts_00022.wav,O ò jẹ́ akẹ́kọ̀ọ́ wavs/yorubatts_00023.wav,Kí wọ́n tó bẹ̀rẹ̀ wavs/yorubatts_00024.wav,Wọ́n jẹun wavs/yorubatts_00025.wav,Àwa ni wavs/yorubatts_00026.wav,A ò jẹ́ oníṣòwò wavs/yorubatts_00027.wav,Mo fẹ́ lọ sí ilé eko wavs/yorubatts_00028.wav,òru wavs/yorubatts_00029.wav,bàtà wavs/yorubatts_00030.wav,Mà jẹun! wavs/yorubatts_00031.wav,A duro títí di òwúrọ̀ wavs/yorubatts_00032.wav,Ṣé o mọ̀ bí a ṣe...? wavs/yorubatts_00033.wav,pàdé wavs/yorubatts_00034.wav,jínnà sí wavs/yorubatts_00035.wav,legbee wavs/yorubatts_00036.wav,Kò sí níbẹ̀ wavs/yorubatts_00037.wav,"To bá ti dáhùn, m ba ti mọ nkan to fẹ́" wavs/yorubatts_00038.wav,Obìnrin kùkùrù wavs/yorubatts_00039.wav,Ẹ̀ ò ní ta a wavs/yorubatts_00040.wav,David bí mí bóyá mo ní owó wavs/yorubatts_00041.wav,Àgọ́ mẹ́ta ni wavs/yorubatts_00042.wav,ṣùgbọ́n wavs/yorubatts_00043.wav,Eyin lo jẹ́ ẹ wavs/yorubatts_00044.wav,Ó yẹ kí n lọ sí ilé ìwòsàn wavs/yorubatts_00045.wav,"Tó bá ti rá oyin, a ba ti fi sí ounje wa" wavs/yorubatts_00046.wav,Èmi ni wavs/yorubatts_00047.wav,Mo ṣiṣẹ́ kí n lè ṣàṣeyọrí wavs/yorubatts_00048.wav,Báwo ni? wavs/yorubatts_00049.wav,Kí n tó jẹun wavs/yorubatts_00050.wav,Ó ń wá gẹ́gẹ́ bó ti wù ú wavs/yorubatts_00051.wav,Mo ti de wavs/yorubatts_00052.wav,Ó n bẹ̀rù wavs/yorubatts_00053.wav,Èwo lo fẹ́? wavs/yorubatts_00054.wav,"Tó bá ti ràn mí lọ́wọ́, m ba ti parí bayìí" wavs/yorubatts_00055.wav,Wọ́n ò ti jẹun wavs/yorubatts_00056.wav,Wọ́n ní ka máa bọ̀ wavs/yorubatts_00057.wav,Ẹ kúrọ̀lẹ́ wavs/yorubatts_00058.wav,Àwa la sare wavs/yorubatts_00059.wav,Iru mọtọ̀ wo ló ní? wavs/yorubatts_00060.wav,David máa ń lo si London ni ọ̀sẹ̀ kookan wavs/yorubatts_00061.wav,Ẹ̀ ò ti sètán wavs/yorubatts_00062.wav,Wọ́n ò ti sètán wavs/yorubatts_00063.wav,tà wavs/yorubatts_00064.wav,Àpò naa wavs/yorubatts_00065.wav,mẹje wavs/yorubatts_00066.wav,ìfẹ̀kúfẹ̀ wavs/yorubatts_00067.wav,Ó yẹ ko mu omi púpọ̀ wavs/yorubatts_00068.wav,lẹ̀yìn wavs/yorubatts_00069.wav,mu wavs/yorubatts_00070.wav,O ò ti jẹun wavs/yorubatts_00071.wav,Àwọn ni wavs/yorubatts_00072.wav,se wavs/yorubatts_00073.wav,"Ta bá lọ, a ò ní pẹ̀ padà" wavs/yorubatts_00074.wav,Ó rò pé a kò ní lọ síbi yẹn. wavs/yorubatts_00075.wav,"Ta bá ti ṣiṣẹ́, a ba ti gba owó" wavs/yorubatts_00076.wav,A n jẹun wavs/yorubatts_00077.wav,Mo maa wa wavs/yorubatts_00078.wav,Wọ́n ò rẹ́rìn wavs/yorubatts_00079.wav,A ò jẹun wavs/yorubatts_00080.wav,O kì í jẹ iresi wavs/yorubatts_00081.wav,Mo máa ń lọ sí ilé ẹ̀kọ́ lẹ́ẹ̀kọ̀ọ̀kan wavs/yorubatts_00082.wav,À kì í ṣe oníṣòwò wavs/yorubatts_00083.wav,Ọkùnrin tó n ṣiṣẹ́ wavs/yorubatts_00084.wav,"Tẹ bá ti fi tọ́kàntọ́kàn ṣiṣẹ́, ẹ̀ ba ti ṣiṣẹ́ pẹ̀lú wa bayìí" wavs/yorubatts_00085.wav,Ẹ̀yin wavs/yorubatts_00086.wav,"Tí wọ́n bá ti ṣiṣẹ́, wọ́n bá ti gba owó" wavs/yorubatts_00087.wav,James fẹ́ ki n má lọ wavs/yorubatts_00088.wav,Mo gbọ́dọ̀ wavs/yorubatts_00089.wav,gbígbóná wavs/yorubatts_00090.wav,"Nígbà naa, ó ń jẹun" wavs/yorubatts_00091.wav,títí di wavs/yorubatts_00092.wav,Mo maa lọ wavs/yorubatts_00093.wav,Mo ní láti wavs/yorubatts_00094.wav,"Ti David bá ti yára, o ba ti wà lọjà bayìí" wavs/yorubatts_00095.wav,"Tó bá ti dé, a ò ba ni ronu" wavs/yorubatts_00096.wav,Ó yẹ ko kòkò jẹun wavs/yorubatts_00097.wav,Ó gbà pé a kò ní lọ síbi yẹn. wavs/yorubatts_00098.wav,bí wavs/yorubatts_00099.wav,tóbi wavs/yorubatts_00100.wav,"Tí wọ́n bá ti bẹ̀rẹ̀ ní kutukutu, wọ́n ba ti parí iṣẹ́" wavs/yorubatts_00101.wav,Ó jẹun wavs/yorubatts_00102.wav,Mo n bo wavs/yorubatts_00103.wav,Iru ilé wo ni yẹn? wavs/yorubatts_00104.wav,Wọ́n sọ pé wọn ti dé. wavs/yorubatts_00105.wav,Mo maa jade wavs/yorubatts_00106.wav,Kò ti sètán wavs/yorubatts_00107.wav,Mo sọ pé ka má ṣiṣẹ́ wavs/yorubatts_00108.wav,Mo n je iresi wavs/yorubatts_00109.wav,Mo máa ṣiṣẹ́ laalẹ́ wavs/yorubatts_00110.wav,Otutu n mu mi wavs/yorubatts_00111.wav,Ẹ̀ ra a wavs/yorubatts_00112.wav,Má jẹ́ kí n lọ wavs/yorubatts_00113.wav,"O máa lọ, àbí?" wavs/yorubatts_00114.wav,A máa jẹun wavs/yorubatts_00115.wav,Awa kọ̀ ló béèrè wavs/yorubatts_00116.wav,Ẹ̀yin n jẹun wavs/yorubatts_00117.wav,Mi o fẹ́ ko lọ wavs/yorubatts_00118.wav,Ẹ dín owó síi wavs/yorubatts_00119.wav,Wọ́n tẹ́tẹ́ dá a lóhùn wavs/yorubatts_00120.wav,Ó wọ ilé gbé apótí jáde wavs/yorubatts_00121.wav,Mo rí wọn wavs/yorubatts_00122.wav,Iwo tabi emi? wavs/yorubatts_00123.wav,A yá owó látí ra ohun èlò wavs/yorubatts_00124.wav,ìfẹ́ wavs/yorubatts_00125.wav,wọn wavs/yorubatts_00126.wav,Wọ́n lọ sí ibudo látí rí aláìlera wavs/yorubatts_00127.wav,Bá mi ṣe ìṣe naa wavs/yorubatts_00128.wav,Mo gbọ́ pé ó fẹ́ràn rẹ. wavs/yorubatts_00129.wav,Mo lè wavs/yorubatts_00130.wav,ìfarapa wavs/yorubatts_00131.wav,pẹ̀lú ìtìjú wavs/yorubatts_00132.wav,Wọ́n ò kùrù wavs/yorubatts_00133.wav,A ní moto wavs/yorubatts_00134.wav,èyí ni ìdí tí wavs/yorubatts_00135.wav,baba wavs/yorubatts_00136.wav,Obìnrin tó kéré wavs/yorubatts_00137.wav,Èmi lo lọ wavs/yorubatts_00138.wav,"Ó rẹ̀, nítorí náà ó sùn" wavs/yorubatts_00139.wav,Mo le bá ọ ṣe wavs/yorubatts_00140.wav,ìrírí wavs/yorubatts_00141.wav,O re mi wavs/yorubatts_00142.wav,Ẹ̀ máa se òbẹ wavs/yorubatts_00143.wav,lábe wavs/yorubatts_00144.wav,Wọ́n máa se òbẹ wavs/yorubatts_00145.wav,mẹ́fà wavs/yorubatts_00146.wav,láì sí wavs/yorubatts_00147.wav,Ko sí eran níbí wavs/yorubatts_00148.wav,"Ta ò bá mura, a ò ní ṣàṣeyọrí" wavs/yorubatts_00149.wav,Mo ti lọ ra ìwé wavs/yorubatts_00150.wav,Ṣé o fẹ́ kí n bá ẹ ra omi? wavs/yorubatts_00151.wav,Kò rẹ́rìn wavs/yorubatts_00152.wav,Ó ra a wavs/yorubatts_00153.wav,Ó mọ̀ bí a ṣe ń kọrin wavs/yorubatts_00154.wav,Emi nko? wavs/yorubatts_00155.wav,Ṣé wọ́n le bá mi ra ounjẹ? wavs/yorubatts_00156.wav,"Tí m bá ní owó, mo màá rà moto" wavs/yorubatts_00157.wav,Otutu wavs/yorubatts_00158.wav,Mi ò mọ̀ wavs/yorubatts_00159.wav,Ó rí mi wavs/yorubatts_00160.wav,tó jẹ́ pé wavs/yorubatts_00161.wav,Óun lo sá wavs/yorubatts_00162.wav,A ò rẹ́rìn wavs/yorubatts_00163.wav,"Tí won bá ti bí mi ní àkókò yẹn, mi ò ní lọ si ilé-ẹ̀kọ́" wavs/yorubatts_00164.wav,Èmi wavs/yorubatts_00165.wav,À kì í gba bọ́ọ̀lù wavs/yorubatts_00166.wav,Mo ní ìfẹ́ rẹ wavs/yorubatts_00167.wav,Ó kì í gboran wavs/yorubatts_00168.wav,Mo n jeun bayii wavs/yorubatts_00169.wav,ìforúkọsílẹ̀ wavs/yorubatts_00170.wav,Mo lọ ra omi wavs/yorubatts_00171.wav,Iru aṣọ wo ló máa ń wọ̀? wavs/yorubatts_00172.wav,Wọ́n máa jẹun wavs/yorubatts_00173.wav,Lẹ́yìn tí wavs/yorubatts_00174.wav,À se oúnjẹ láì niyọ̀ wavs/yorubatts_00175.wav,A ò mọ̀ bí a ṣe ń ṣe é wavs/yorubatts_00176.wav,"A máa dé, o dájú" wavs/yorubatts_00177.wav,Ó ṣiṣẹ́ dáadáa tó jẹ́ pé gbogbo ènìyàn yìn ín wavs/yorubatts_00178.wav,ṣe wavs/yorubatts_00179.wav,O ṣéé ṣé wavs/yorubatts_00180.wav,A lọ kàwé wavs/yorubatts_00181.wav,Ó lọ làná wavs/yorubatts_00182.wav,Ka tó sọ̀rọ̀ wavs/yorubatts_00183.wav,Èwo ni ilé rẹ? wavs/yorubatts_00184.wav,Jẹun! wavs/yorubatts_00185.wav,"Ta bá ti yára, a ba ti wà lọjà bayìí" wavs/yorubatts_00186.wav,A ra a wavs/yorubatts_00187.wav,rà wavs/yorubatts_00188.wav,Mo kùrù wavs/yorubatts_00189.wav,Mi ò rẹ́rìn wavs/yorubatts_00190.wav,"Te ba ra moto, e pe mi fun ayeye" wavs/yorubatts_00191.wav,Kí ni ìṣòro náà? wavs/yorubatts_00192.wav,Mo máa ń lọ lẹ́ẹ̀kọ̀ọ̀kan wavs/yorubatts_00193.wav,Lẹ́yìn náà wavs/yorubatts_00194.wav,àtijọ́ wavs/yorubatts_00195.wav,"Tí m bá ti ṣiṣẹ́, m ba ti ní owó bayìí" wavs/yorubatts_00196.wav,Mo ra aṣọ nítorí pé mo ní owó wavs/yorubatts_00197.wav,Mo gbàdúrà ka má ṣe aṣìṣe wavs/yorubatts_00198.wav,Ó wà ní ilé wavs/yorubatts_00199.wav,èrè wavs/yorubatts_00200.wav,Ó jẹ́ ìrírí ayọ̀ fún mi wavs/yorubatts_00201.wav,ni ìdákẹ́jẹ wavs/yorubatts_00202.wav,O ṣéé ṣé kí n le ra wavs/yorubatts_00203.wav,Ó máa ń jẹun lojoojumo wavs/yorubatts_00204.wav,Mo sọ fún un kó má ṣe é mọ́ wavs/yorubatts_00205.wav,A ò ti sètán wavs/yorubatts_00206.wav,wá wavs/yorubatts_00207.wav,lojoojumo wavs/yorubatts_00208.wav,Mo lọ mu omi wavs/yorubatts_00209.wav,gbe wavs/yorubatts_00210.wav,Ó sáré bí ẹni tí olopaa ń lé wavs/yorubatts_00211.wav,David ni iba wavs/yorubatts_00212.wav,Ọmọ tó dáa wavs/yorubatts_00213.wav,"Ta bá ti ṣiṣẹ́, a ba ti gba owó" wavs/yorubatts_00214.wav,Èmi kọ́ ni olùkó wavs/yorubatts_00215.wav,ṣùgbọ́n wavs/yorubatts_00216.wav,Ẹ kú ọdún wavs/yorubatts_00217.wav,A gbàdúrà kí wọ́n lè ṣàṣeyọrí wavs/yorubatts_00218.wav,Mi ò jẹ́ olùkó wavs/yorubatts_00219.wav,Mo máa jẹun wavs/yorubatts_00220.wav,Mo ti lọ wavs/yorubatts_00221.wav,Ó wí pé a kò ní lọ síbi yẹn. wavs/yorubatts_00222.wav,Ó ń bínú wavs/yorubatts_00223.wav,"Tí mi ò bá ti lọ, mi o ba ní rí i" wavs/yorubatts_00224.wav,Ìwọ lo bẹ̀rẹ̀ wavs/yorubatts_00225.wav,A ti lọ wavs/yorubatts_00226.wav,Mo béèrè bóyá ó ti lọ wavs/yorubatts_00227.wav,Ó ní kí n lọ wavs/yorubatts_00228.wav,Má jẹ́ kí ó jẹun wavs/yorubatts_00229.wav,"Mo ní owó, nítorí náà mo ra aṣọ" wavs/yorubatts_00230.wav,Tẹ́tẹ́ dá a lóhùn wavs/yorubatts_00231.wav,Inu mi ń dun mí wavs/yorubatts_00232.wav,Mo lọ sí ọjà pẹ̀lú ọ̀rẹ́ mi wavs/yorubatts_00233.wav,súnmo wavs/yorubatts_00234.wav,Ẹ̀yin kọ̀ wavs/yorubatts_00235.wav,Kò yẹ kó ṣiṣẹ́ lónìí wavs/yorubatts_00236.wav,Ó sọ̀rọ̀ ni ìdákẹ́jẹ wavs/yorubatts_00237.wav,Ọwọ́ wavs/yorubatts_00238.wav,"To ba je àwọn, wọ́n ò ní yá owó" wavs/yorubatts_00239.wav,pẹ̀lú ibinnu wavs/yorubatts_00240.wav,Mi ò jẹun wavs/yorubatts_00241.wav,Ó yẹ kó sinmi wavs/yorubatts_00242.wav,Àwa wavs/yorubatts_00243.wav,Àwa fẹ́ kí wọ́n bọ̀ láàyè wavs/yorubatts_00244.wav,Ẹran wà níbẹ̀ wavs/yorubatts_00245.wav,Mo fẹ́ràn èso bí ògẹ̀dẹ̀ àti ọ̀sán wavs/yorubatts_00246.wav,mẹ́ta wavs/yorubatts_00247.wav,Ó ní kí wọn má pariwo wavs/yorubatts_00248.wav,Ọmọ ọdún mélòó ni ọ? wavs/yorubatts_00249.wav,Ó mọ̀ bí won ṣe ṣé wavs/yorubatts_00250.wav,je wavs/yorubatts_00251.wav,Kò gbọ́ rárá wavs/yorubatts_00252.wav,Ó lọ láì kí ẹnikẹ́ni wavs/yorubatts_00253.wav,gan-an wavs/yorubatts_00254.wav,Etí wavs/yorubatts_00255.wav,"Nígbà naa, ó ń jẹun" wavs/yorubatts_00256.wav,pupo wavs/yorubatts_00257.wav,Báwo ni mo ṣe le ràn ẹ́ lọwọ? wavs/yorubatts_00258.wav,ọmọ wavs/yorubatts_00259.wav,Ẹ̀ ò ti jẹun wavs/yorubatts_00260.wav,Kó tó sùn wavs/yorubatts_00261.wav,kíákíá wavs/yorubatts_00262.wav,ọ̀kan wavs/yorubatts_00263.wav,Wọ́n máa jẹun ni ọ̀sán wavs/yorubatts_00264.wav,O ò ní ta a wavs/yorubatts_00265.wav,O jẹun wavs/yorubatts_00266.wav,Àgọ́ mélòó lo lu? wavs/yorubatts_00267.wav,O kì í ṣe akẹ́kọ̀ọ́ wavs/yorubatts_00268.wav,O ra a wavs/yorubatts_00269.wav,A bẹ̀rẹ̀ látí kọ́ ìtàn Yorùbá wavs/yorubatts_00270.wav,ajọyọ̀ wavs/yorubatts_00271.wav,Ṣé wọ́n mọ̀ bí a ṣe ń taja? wavs/yorubatts_00272.wav,À ò burú wavs/yorubatts_00273.wav,àti wavs/yorubatts_00274.wav,"Tójo bá rọ̀, mi ò ní lọ" wavs/yorubatts_00275.wav,Kí ni wọ́n fẹ́? wavs/yorubatts_00276.wav,Báwo lo ṣe fẹ́? wavs/yorubatts_00277.wav,A máa se òbẹ wavs/yorubatts_00278.wav,David lo jẹ́ ẹ wavs/yorubatts_00279.wav,ayọ̀ wavs/yorubatts_00280.wav,"To bá ti wá, a ò bá ní ronu" wavs/yorubatts_00281.wav,Ó sáré ra ewé wavs/yorubatts_00282.wav,Èmi n jẹun wavs/yorubatts_00283.wav,Ṣé ó wà ní ilé? wavs/yorubatts_00284.wav,Ṣe ìse amurele rẹ! wavs/yorubatts_00285.wav,Mo fẹ́ kó ṣàseyọrí wavs/yorubatts_00286.wav,A ò ti jẹun wavs/yorubatts_00287.wav,Kò ṣéé ṣé wavs/yorubatts_00288.wav,Ta lo ṣe yen? wavs/yorubatts_00289.wav,Báwo lo ṣe ṣe? wavs/yorubatts_00290.wav,O ò ti sètán wavs/yorubatts_00291.wav,Inú mi bàjẹ́ wavs/yorubatts_00292.wav,Mi ò ní jẹun wavs/yorubatts_00293.wav,Inú rẹ bàjẹ́ wavs/yorubatts_00294.wav,Ẹ káàrọ̀ wavs/yorubatts_00295.wav,"Tele, mo máa ń sáré lojoojúmọ́" wavs/yorubatts_00296.wav,kéré wavs/yorubatts_00297.wav,"Tí m bá ti kàwé, m ba ti yẹ́gé" wavs/yorubatts_00298.wav,ìlú wavs/yorubatts_00299.wav,O rin pelu ibinnu wavs/yorubatts_00300.wav,Ọri n fo mi wavs/yorubatts_00301.wav,O ti jẹun wavs/yorubatts_00302.wav,ẹnu wavs/yorubatts_00303.wav,Mo mọ̀ bí ó ṣe ṣe wavs/yorubatts_00304.wav,Ìwọ wavs/yorubatts_00305.wav,Ọmọkùnrin gíga wavs/yorubatts_00306.wav,Mo joko pelu Jane wavs/yorubatts_00307.wav,Mo ga wavs/yorubatts_00308.wav,Mo fẹ́ wavs/yorubatts_00309.wav,Ìtàn náà bà mí nínú wavs/yorubatts_00310.wav,Ṣé o fẹ́ lọ? wavs/yorubatts_00311.wav,Bàtà yìí wavs/yorubatts_00312.wav,gbà wavs/yorubatts_00313.wav,"Ta bá ṣiṣẹ́, a máa rí èrè" wavs/yorubatts_00314.wav,marún wavs/yorubatts_00315.wav,àlàáfíà wavs/yorubatts_00316.wav,Ẹ Jẹun! wavs/yorubatts_00317.wav,Ó kawé kó lè yẹ́gé ní ìdánwò wavs/yorubatts_00318.wav,àjálù wavs/yorubatts_00319.wav,Ó n jẹun wavs/yorubatts_00320.wav,síi wavs/yorubatts_00321.wav,Inú wa dùn gan-an wavs/yorubatts_00322.wav,ṣáájú wavs/yorubatts_00323.wav,Ó wà níbí wavs/yorubatts_00324.wav,Ó gbàdúrà kí ìyàwó rẹ̀ rí àlàáfíà wavs/yorubatts_00325.wav,"Nítorí pé mo ní owó, mo ra aṣọ" wavs/yorubatts_00326.wav,Mo lọ ra ìwé wavs/yorubatts_00327.wav,kòkò wavs/yorubatts_00328.wav,Kò ní jẹun wavs/yorubatts_00329.wav,"Mo fẹ́ lọ, ṣùgbọ́n mi ò ní owó" wavs/yorubatts_00330.wav,"To ba ni owó, mi o ni be o" wavs/yorubatts_00331.wav,Nigbà wo lo máa lọ? wavs/yorubatts_00332.wav,Ṣé wọ́n lè ṣiṣẹ́? wavs/yorubatts_00333.wav,nítorí pé wavs/yorubatts_00334.wav,Mo ní kí wọn má bá wa wí wavs/yorubatts_00335.wav,Ó ti lọ ni ojo meji to koja wavs/yorubatts_00336.wav,mẹ́sán wavs/yorubatts_00337.wav,Má jẹ́ kó jẹun wavs/yorubatts_00338.wav,ìtùnú wavs/yorubatts_00339.wav,Kí ló dé? wavs/yorubatts_00340.wav,Ó wá rà ọkọ̀ wavs/yorubatts_00341.wav,"Tí m bá ní owó, mi ò ní fi sílẹ̀" wavs/yorubatts_00342.wav,"To ò bá ti wá, a ò bá ní bẹ̀rù" wavs/yorubatts_00343.wav,Mo ra a wavs/yorubatts_00344.wav,À ò tobi wavs/yorubatts_00345.wav,kùkùrù wavs/yorubatts_00346.wav,A ò ní ta a wavs/yorubatts_00347.wav,Èmi ni olùkọ́ wavs/yorubatts_00348.wav,Kò ṣéé ṣé kó ṣẹlẹ̀ wavs/yorubatts_00349.wav,Mo n jẹun wavs/yorubatts_00350.wav,Wọ́n máa wá ni òwúrọ̀ wavs/yorubatts_00351.wav,Ó le bá mi ṣiṣẹ́ wavs/yorubatts_00352.wav,Mo béèrè pé Ṣé ó ti lọ? wavs/yorubatts_00353.wav,kankan wavs/yorubatts_00354.wav,Wọ́n ò ní jẹun wavs/yorubatts_00355.wav,lórí wavs/yorubatts_00356.wav,"To ba je ìwọ , o ò ní jẹ́ kí wọ́n fẹ̀sùn kàn ọ" wavs/yorubatts_00357.wav,"Tí kò bá ti wá, a ò ba ní gbà á" wavs/yorubatts_00358.wav,A wọlé pẹ̀lú ìtìjú wavs/yorubatts_00359.wav,tuntun wavs/yorubatts_00360.wav,Mi ò ní ta a wavs/yorubatts_00361.wav,Ó tèlé wa wavs/yorubatts_00362.wav,ni ọ̀sẹ̀ kookan wavs/yorubatts_00363.wav,Mo fẹ́ kí wọn má wá síbí wavs/yorubatts_00364.wav,Bá mi ra moto naa wavs/yorubatts_00365.wav,Ìwé wà níbí wavs/yorubatts_00366.wav,Awọ́n kọ́ ni ọ̀lọ́́jọ́gbọ́n wavs/yorubatts_00367.wav,ìdílé wavs/yorubatts_00368.wav,"Jọ̀wọ́, kọ́ wa bí a ṣe ń sọ Yorùbá" wavs/yorubatts_00369.wav,Jẹ́ ko sùn wavs/yorubatts_00370.wav,O ò ní jẹun wavs/yorubatts_00371.wav,Ó wà níbẹ̀ wavs/yorubatts_00372.wav,Mo mọ̀ bí ó ṣe lè ṣe é wavs/yorubatts_00373.wav,Ẹ kaàbọ̀ wavs/yorubatts_00374.wav,Mo mọ̀ bí wọ́n ṣe ṣé wavs/yorubatts_00375.wav,gẹ́gẹ́ bí wavs/yorubatts_00376.wav,Àgọ́ márùn kọja ìsẹ́jú mẹ́wà wavs/yorubatts_00377.wav,"Tí mi ò bá lọ, ó máa bínú" wavs/yorubatts_00378.wav,Mi kì í jẹ ewa wavs/yorubatts_00379.wav,"Tó bá ti kọ́ ẹ̀kọ́ dáadáa, ó ba ti mọ nkan tí wọ́n ń sọ" wavs/yorubatts_00380.wav,Ó sọ̀rọ̀ bí agbẹjọ́rò wavs/yorubatts_00381.wav,A ti jẹun wavs/yorubatts_00382.wav,"Lẹ́yìn tí mo jẹun, mo lọ sùn." wavs/yorubatts_00383.wav,"To bá lọ sí London, o máa gbádùn" wavs/yorubatts_00384.wav,Ó máa jẹun wavs/yorubatts_00385.wav,Ó dára jùlọ wavs/yorubatts_00386.wav,Ẹ n jẹun wavs/yorubatts_00387.wav,Èmi kọ̀ wavs/yorubatts_00388.wav,Mi ò ga wavs/yorubatts_00389.wav,Àṣọ yìí dára ju ti yẹn lọ wavs/yorubatts_00390.wav,ìtẹ́lọ́rùn wavs/yorubatts_00391.wav,Èyí ni ìdí tí mo fi lọ wavs/yorubatts_00392.wav,Iba wavs/yorubatts_00393.wav,Jẹun síi wavs/yorubatts_00394.wav,Inú wavs/yorubatts_00395.wav,pẹ̀lú wavs/yorubatts_00396.wav,A kòkò jẹun ka tó lọ wavs/yorubatts_00397.wav,Ó yẹ kí wọn tẹ́tẹ́ fi han wavs/yorubatts_00398.wav,Wọ́n ra a wavs/yorubatts_00399.wav,Mo mọ̀ bí a ṣe ń dana wavs/yorubatts_00400.wav,Òun n jẹun wavs/yorubatts_00401.wav,tún wavs/yorubatts_00402.wav,"Tí wọ́n bá pe mi, mo màá wa" wavs/yorubatts_00403.wav,Obìnrin tó kùrù wavs/yorubatts_00404.wav,so wavs/yorubatts_00405.wav,Òun wavs/yorubatts_00406.wav,"Ta bá ti lọ sí ilé-ẹ̀kọ́, a ba ti gbọ́ ìtàn náà bayìí" wavs/yorubatts_00407.wav,tẹ́tẹ́ wavs/yorubatts_00408.wav,Bàtà mi wavs/yorubatts_00409.wav,Ó bí mí bóyá mo ní owó wavs/yorubatts_00410.wav,O máa jẹun wavs/yorubatts_00411.wav,A ń ṣiṣẹ́ nígbà náà wavs/yorubatts_00412.wav,àbí wavs/yorubatts_00413.wav,Tún Ṣe wavs/yorubatts_00414.wav,Wọ́n máa lọ ni odun to n bo wavs/yorubatts_00415.wav,Wọ́n lè ṣeré wavs/yorubatts_00416.wav,Mo fẹ́ pe ẹ̀ wavs/yorubatts_00417.wav,Ẹ káàsán wavs/yorubatts_00418.wav,Kò burú wavs/yorubatts_00419.wav,Ilé wa wavs/yorubatts_00420.wav,Ó ní ilé wavs/yorubatts_00421.wav,Mo sọ pé kí wọn má ṣiṣẹ́ wavs/yorubatts_00422.wav,Wọ́n ò mọ̀ bí a ṣe ń kàwé wavs/yorubatts_00423.wav,Ìwọ ni wavs/yorubatts_00424.wav,"Nígbà tí mo dé, ó ń jẹun" wavs/yorubatts_00425.wav,Mi ò ní jẹun kankan wavs/yorubatts_00426.wav,"To bá ti wá, a ò ní bẹ̀rù" wavs/yorubatts_00427.wav,"To ò bá kawe, o ò ní yege" wavs/yorubatts_00428.wav,Inú mi dùn wavs/yorubatts_00429.wav,Ó gbagbo pé a kò ní lọ síbi yẹn. wavs/yorubatts_00430.wav,Ó maa ń ṣiṣẹ́ nigbagbogbo wavs/yorubatts_00431.wav,O ò rẹ́rìn wavs/yorubatts_00432.wav,O n jẹun wavs/yorubatts_00433.wav,Kí ni orúkọ rẹ? wavs/yorubatts_00434.wav,mẹ́rin wavs/yorubatts_00435.wav,owó wavs/yorubatts_00436.wav,"Nítorí pé mo ní owó, mo ra aṣọ tuntun" wavs/yorubatts_00437.wav,Mo máa lọ ra oúnjẹ wavs/yorubatts_00438.wav,Ìyá àti Bàbá wà nílé wavs/yorubatts_00439.wav,A jẹun wavs/yorubatts_00440.wav,Ó máa se òbẹ wavs/yorubatts_00441.wav,Ó ò ní ṣiṣẹ́ mọ̀ wavs/yorubatts_00442.wav,gíga wavs/yorubatts_00443.wav,Mo fẹ́ ko má lọ wavs/yorubatts_00444.wav,Mo le bà e ra omi wavs/yorubatts_00445.wav,Kọ́ mi bí a ṣe ń bù ọbẹ̀ wavs/yorubatts_00446.wav,Wọ́n mú ẹran jẹ wavs/yorubatts_00447.wav,Bàtà yìí kéré jùlọ wavs/yorubatts_00448.wav,ìṣòro wavs/yorubatts_00449.wav,mẹ́wà wavs/yorubatts_00450.wav,"To ò bá ti wá, a ò bá ní bẹ̀rù" wavs/yorubatts_00451.wav,Mo lọ ra ìwé wavs/yorubatts_00452.wav,Ilé yẹn wavs/yorubatts_00453.wav,Mo tobi wavs/yorubatts_00454.wav,burúkú wavs/yorubatts_00455.wav,Mo máa ń jeun gan-an nigba ti mo kere. wavs/yorubatts_00456.wav,rẹ́rìn músẹ̀ wavs/yorubatts_00457.wav,Àwa lọ rí bàbá wa wavs/yorubatts_00458.wav,Ó jẹ́ dollar marun wavs/yorubatts_00459.wav,Ó n jẹun wavs/yorubatts_00460.wav,ogún wavs/yorubatts_00461.wav,Mo máa ń lọ sí ilé ẹ̀kọ́. wavs/yorubatts_00462.wav,Nígbà náà wavs/yorubatts_00463.wav,Ìrìnàjò náà dùn mo mi gan-an wavs/yorubatts_00464.wav,Oun lo béèrè wavs/yorubatts_00465.wav,Ẹ ò jẹ́ olórin wavs/yorubatts_00466.wav,ẹni wavs/yorubatts_00467.wav,Mo máa ṣiṣẹ́ laalẹ́ wavs/yorubatts_00468.wav,Awon bàtà yìí wavs/yorubatts_00469.wav,Mo ní ìbànújẹ wavs/yorubatts_00470.wav,Ta lo wa níta? wavs/yorubatts_00471.wav,Níbo ni ilé rẹ? wavs/yorubatts_00472.wav,Ó gbọ́dọ̀ ṣiṣẹ́ wavs/yorubatts_00473.wav,Bàtà wà níbẹ̀ wavs/yorubatts_00474.wav,Ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ wavs/yorubatts_00475.wav,David kọ̀ ló wá wavs/yorubatts_00476.wav,Iru bàtà wo le rà? wavs/yorubatts_00477.wav,Mo ní ko kawé wavs/yorubatts_00478.wav,Bá mi kọ́wé wavs/yorubatts_00479.wav,Ẹ kúúṣẹ́ wavs/yorubatts_00480.wav,Apá mi ń dun mi wavs/yorubatts_00481.wav,David ga ju James lọ wavs/yorubatts_00482.wav,níwájú wavs/yorubatts_00483.wav,David ni wavs/yorubatts_00484.wav,Mo ṣe é gẹ́gẹ́ bí àṣẹ rẹ wavs/yorubatts_00485.wav,Ẹ̀ kì í ṣe olórin wavs/yorubatts_00486.wav,Ẹ jọ̀ọ́ ẹ jẹun wavs/yorubatts_00487.wav,Ẹ̀yin kọ́ ni olórin wavs/yorubatts_00488.wav,Ó jó bí ẹni tí kì í rẹ́ wavs/yorubatts_00489.wav,"Ta ò bá ti ṣiṣẹ́, a ò ba ní ra ile" wavs/yorubatts_00490.wav,Àwa n jẹun wavs/yorubatts_00491.wav,Níbo ni Janet wà? wavs/yorubatts_00492.wav,Jẹ́ kí n ràn ẹ́ lọ́wọ́ wavs/yorubatts_00493.wav,Ilé yin wavs/yorubatts_00494.wav,Jẹ́ kó jẹun wavs/yorubatts_00495.wav,Ìjọsìn yìí mú inú mi dùn wavs/yorubatts_00496.wav,Mi o rántí bóyá o jẹun wavs/yorubatts_00497.wav,gidigidi wavs/yorubatts_00498.wav,"Tí wọ́n bá ti mọ̀, wọ́n ò ní kọ́sẹ̀" wavs/yorubatts_00499.wav,Níbo ni wọ́n lọ? wavs/yorubatts_00500.wav,Wọ́n wá látí ṣèrànwọ́ wavs/yorubatts_00501.wav,Nígbà ti wavs/yorubatts_00502.wav,Ilé yìí tóbi ju ti wọ́n wavs/yorubatts_00503.wav,Èló ni bàtà yìí? wavs/yorubatts_00504.wav,Orúkọ mi ni... wavs/yorubatts_00505.wav,Wọ́n ò jẹun wavs/yorubatts_00506.wav,Wọ́n n jẹun wavs/yorubatts_00507.wav,Má jẹ́ kó sùn wavs/yorubatts_00508.wav,Bàtà rẹ̀ wavs/yorubatts_00509.wav,Ó fẹ́ràn rẹ púpọ̀ wavs/yorubatts_00510.wav,láì wavs/yorubatts_00511.wav,"Nigba ti mo dé, mo rí i" wavs/yorubatts_00512.wav,Mo ti jẹun wavs/yorubatts_00513.wav,Ṣé o lè ràn mí lọ́wọ́? wavs/yorubatts_00514.wav,Ẹsẹ̀ wavs/yorubatts_00515.wav,Àwa kọ́ ni oníṣòwò wavs/yorubatts_00516.wav,"Tí ìwọ bá lọ sí London, o máa gbádùn" wavs/yorubatts_00517.wav,A kòkò jẹun ka tó lọ wavs/yorubatts_00518.wav,Wọ́n rìn-àjò láì sí James wavs/yorubatts_00519.wav,"Ti Janet ko bá ti ràn mí lọ́wọ́, m ba ti jìyà" wavs/yorubatts_00520.wav,tàbí wavs/yorubatts_00521.wav,Mo fẹ́ ko tẹ́tẹ́ sáré wavs/yorubatts_00522.wav,Mo máa lọ lónìí wavs/yorubatts_00523.wav,Bàtà wà lábẹ̀ ibùsùn wavs/yorubatts_00524.wav,pẹ̀lú wavs/yorubatts_00525.wav,Ẹsẹ̀ mi ń dun mi wavs/yorubatts_00526.wav,mẹjọ wavs/yorubatts_00527.wav,Kí ni ìdí tí a ra moto? wavs/yorubatts_00528.wav,David kọ́ ni olùkó wavs/yorubatts_00529.wav,A mọ̀ bí a ṣe ń jó wavs/yorubatts_00530.wav,Mo ní ìtẹ́lọ́rùn wavs/yorubatts_00531.wav,Mo sáré kíákíá wavs/yorubatts_00532.wav,Iru àpò wo ló ní? wavs/yorubatts_00533.wav,nigbagbogbo wavs/yorubatts_00534.wav,Wọ́n máa lọ ni ose to n bo wavs/yorubatts_00535.wav,Mo jẹ́ ọmọ ọdún méjìlá wavs/yorubatts_00536.wav,gẹ́gẹ́ bí wavs/yorubatts_00537.wav,eré wavs/yorubatts_00538.wav,"Ẹ jọ̀ọ́, jẹ́ kí n wọlé" wavs/yorubatts_00539.wav,Mo fẹ́ran ẹ wavs/yorubatts_00540.wav,tó fi jẹ́ pé wavs/yorubatts_00541.wav,Kò mọ̀ bí a ṣe ń kọrin wavs/yorubatts_00542.wav,Ó ò jẹ́ olùkó wavs/yorubatts_00543.wav,Ikọ wavs/yorubatts_00544.wav,Mo jẹun wavs/yorubatts_00545.wav,"To ba je emi, mi ò ní fọwọ́sowọpọ̀" wavs/yorubatts_00546.wav,Ẹ káalẹ́ wavs/yorubatts_00547.wav,itura wavs/yorubatts_00548.wav,wọn wavs/yorubatts_00549.wav,Tẹ́lẹ̀ wavs/yorubatts_00550.wav,Wọ́n ò lọ rárá wavs/yorubatts_00551.wav,David bẹ̀ mi pé kí n má bínú wavs/yorubatts_00552.wav,nigbagbogbo wavs/yorubatts_00553.wav,Iru ounjẹ wo la fẹ́ràn? wavs/yorubatts_00554.wav,Wọ́n máa lọ ni ojo meji to n bo wavs/yorubatts_00555.wav,Óun kọ̀ ló wá wavs/yorubatts_00556.wav,Ko tó lọ wavs/yorubatts_00557.wav,Ìrírí yìí mú kí n ronú wavs/yorubatts_00558.wav,Wọ́n ti jẹun wavs/yorubatts_00559.wav,Ẹ jọ̀ọ́ wavs/yorubatts_00560.wav,Èwo ni wọ́n ra? wavs/yorubatts_00561.wav,Ó yẹ ka jẹun ní àkókò wavs/yorubatts_00562.wav,Ta ni? wavs/yorubatts_00563.wav,"Tó bá ti dé, a ò ba ni ronu" wavs/yorubatts_00564.wav,Mo fẹ́ kọ́ ẹ̀kọ́ látí di dókítà wavs/yorubatts_00565.wav,Ẹ̀yin ni wavs/yorubatts_00566.wav,Ko sí fonu níbí wavs/yorubatts_00567.wav,Kí ni ìdí tí o fe lọ? wavs/yorubatts_00568.wav,Ó ti jẹun wavs/yorubatts_00569.wav,Orí wavs/yorubatts_00570.wav,"Tó ò bá pè, a ò ní mọ̀" wavs/yorubatts_00571.wav,Iru orin wo ni wọ́n ń kọ? wavs/yorubatts_00572.wav,Mi ò ní pé dé wavs/yorubatts_00573.wav,Mo fẹ́ ọbẹ tàbí ìrẹsì wavs/yorubatts_00574.wav,Ó lọ ni ojo meji to koja wavs/yorubatts_00575.wav,Ó kì í ṣe olùkó wavs/yorubatts_00576.wav,Ó yẹ ka kòkò gbà á wavs/yorubatts_00577.wav,Àwọn n jẹun wavs/yorubatts_00578.wav,Bàbá náà ní kí n ra ewé wavs/yorubatts_00579.wav,lọ wavs/yorubatts_00580.wav,"Tí wọ́n bá fẹ́, wọ́n ò ní kúrò" wavs/yorubatts_00581.wav,Mo wà dáadáa wavs/yorubatts_00582.wav,Ẹ̀ kì í kọrin wavs/yorubatts_00583.wav,Olùkọ́ ní kí àwọn akẹ́kọ̀ọ́ kọ́wé wavs/yorubatts_00584.wav,"A rà oúnjẹ bí àmàlà, ìyán àti ẹ̀bà" wavs/yorubatts_00585.wav,Mo mọ̀ wavs/yorubatts_00586.wav,"Tí m bá ti kówó pamo, m ba ti ra moto bayìí" wavs/yorubatts_00587.wav,Mi kì í ṣe olùkó wavs/yorubatts_00588.wav,Ó yẹ kí wọ́n lọ sùn wavs/yorubatts_00589.wav,bí wavs/yorubatts_00590.wav,Mo ní láti ra ilé wavs/yorubatts_00591.wav,Wọ́n ò ní ta a wavs/yorubatts_00592.wav,ìrora wavs/yorubatts_00593.wav,Ìwọ n jẹun wavs/yorubatts_00594.wav,Ìwọ wavs/yorubatts_00595.wav,òwò wavs/yorubatts_00596.wav,Má jẹ́ kí o sùn wavs/yorubatts_00597.wav,ẹja wavs/yorubatts_00598.wav,Ṣé o le bá mi ṣe? wavs/yorubatts_00599.wav,iṣu wavs/yorubatts_00600.wav,Ẹ̀ máa jẹun wavs/yorubatts_00601.wav,mo wavs/yorubatts_00602.wav,O ò jẹun wavs/yorubatts_00603.wav,Ìwọ lọ ṣáájú wavs/yorubatts_00604.wav,Orí fìfọ wavs/yorubatts_00605.wav,Mo ń jẹun làná wavs/yorubatts_00606.wav,Ko sí iwe lori tabili wavs/yorubatts_00607.wav,Mo kéré wavs/yorubatts_00608.wav,ìbànújẹ wavs/yorubatts_00609.wav,Mo bẹ̀ ọ pé ko má bínú wavs/yorubatts_00610.wav,Bóyá a máa rí David lọ́la wavs/yorubatts_00611.wav,Kò jẹun wavs/yorubatts_00612.wav,méjì wavs/yorubatts_00613.wav,"Lẹ́yìn náà, mo ń ṣiṣẹ́ ní ọ́fíìsì" wavs/yorubatts_00614.wav,Kò ti jẹun wavs/yorubatts_00615.wav,lẹ́ẹ̀kọ̀ọ̀kan wavs/yorubatts_00616.wav,O máa se òbẹ wavs/yorubatts_00617.wav,"To bá ti wá, a ò bá ní jáde" wavs/yorubatts_00618.wav,Nigbà wo ni ìdánwò náà? wavs/yorubatts_00619.wav,"Ó ṣiṣẹ́ takuntakun, tó fi jẹ́ pé wọ́n fún un ní ẹ̀bùn" wavs/yorubatts_00620.wav,tún wavs/yorubatts_00621.wav,"Jọ̀wọ́, kọ́ mi bí a ṣe" wavs/yorubatts_00622.wav,"Tó bá ṣiṣẹ́, kò ní jìyà" wavs/yorubatts_00623.wav,Ṣé o mọ̀ bí a ṣe ń kọrin? wavs/yorubatts_00624.wav,Bàtà wọn wavs/yorubatts_00625.wav,"Tí ẹ bá ti kọ́ ẹ̀kọ́, ẹ ò ní gbagbé" wavs/yorubatts_00626.wav,Jẹ́ kí n lọ wavs/yorubatts_00627.wav,Ẹ ò tóbi wavs/yorubatts_00628.wav,Wọ́n fẹ́ ka ṣiṣẹ́ pọ̀ wavs/yorubatts_00629.wav,Ó dàbọ̀ wavs/yorubatts_00630.wav,Wọ́n kì í ṣiṣẹ́ níbí wavs/yorubatts_00631.wav,òdo wavs/yorubatts_00632.wav,wọn wavs/yorubatts_00633.wav,Ẹ̀ ti lọ wavs/yorubatts_00634.wav,nítorí náà wavs/yorubatts_00635.wav,Mi ò ti sètán wavs/yorubatts_00636.wav,Kẹ tó dé wavs/yorubatts_00637.wav,Bàtà pupa wavs/yorubatts_00638.wav,Ẹ̀ ò ní jẹun wavs/yorubatts_00639.wav,ìlù wavs/yorubatts_00640.wav,dájú wavs/yorubatts_00641.wav,tẹ́tẹ́ wavs/yorubatts_00642.wav,Nigbà wo ni wọ́n dé? wavs/yorubatts_00643.wav,Mo máa se òbẹ wavs/yorubatts_00644.wav,Ó bí mí pé ṣé mo mọ ọ wavs/yorubatts_00645.wav,ninu wavs/yorubatts_00646.wav,réré wavs/yorubatts_00647.wav,A ò ní jẹun wavs/yorubatts_00648.wav,Mo mọ̀ ọ gan-an wavs/yorubatts_00649.wav,Bá wa pa ina wavs/yorubatts_00650.wav,Mo wá láti London wavs/yorubatts_00651.wav,Ìwọ kọ́ ni akẹ́kọ̀ọ́ wavs/yorubatts_00652.wav,Kò ní ta a wavs/yorubatts_00653.wav,Ṣé mo lè rí i? wavs/yorubatts_00654.wav,Kò sí níbí wavs/yorubatts_00655.wav,Awon lo jẹ́ ẹ wavs/yorubatts_00656.wav,rárá wavs/yorubatts_00657.wav,Àwọn wavs/yorubatts_00658.wav,Wọ́n kì í ṣe ọlọ́jọ́gbọ́n wavs/yorubatts_00659.wav,igi wavs/yorubatts_00660.wav,Ìwé wà lórí tábìlì wavs/yorubatts_00661.wav,Mo joko laarin won wavs/yorubatts_00662.wav,Wọ́n ò jẹ́ ọlọ́jọ́gbọ́n wavs/yorubatts_00663.wav,Mi ò ti jẹun wavs/yorubatts_00664.wav,Tẹ́tẹ́ lọ! wavs/yorubatts_00665.wav,Wọ́n rìn-àjò láì sí owó wavs/yorubatts_00666.wav,Mo jẹ́ akẹ́kọ̀ọ́ wavs/yorubatts_00667.wav,Ó ṣe iṣẹ́ rẹ gẹ́gẹ́ bí mo ti sọ wavs/yorubatts_00668.wav,Aga wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ tábìlì wavs/yorubatts_00669.wav,wọn