raw_text
stringlengths
2
128k
ahmed ahmed ahmed ahmed lárúbáwá ‎ tí wọ́n bí ní june 27 1970 jẹ́ ọmọ orílẹ̀ èdè america tó tan mọ́ ilẹ̀ egypt tó jẹ́ òṣèrékùnrin àti apanilẹ́rìn-ín
sohail ahmed sohail ahmed pùnjábì tí wọ́n bí ní 1 may 1963 tó tún ń jẹ́ azizi urdu jẹ́ òṣèrékùnrin apanilẹ́rìn-ín àti olùdarí fíìmù ti ilẹ̀ pakístàn
franklyn ajaye franklyn ajaye tí wọ́n bí ní may 13 1949 jẹ́ apanilẹ́rìn-ín òṣèrékùnrin àti òǹkọ̀wé ti orílẹ̀ èdè america
anna akana anna kay napualani akana tí wọ́n bí ní august 18 1989 jẹ́ òṣèrébìnrin apanilẹ́rìn-ín olórin òṣìṣẹ́ lórí àtiyoutube ó ti ṣàfihàn lórí fíìmù orí ẹ̀rọ-amóhùnmáwòrán fíìmù àti orin
nasser al qasabi nasser bin qassim al qasabi lárúbáwá ‎ tí wọ́n bí ní 28 november 1961 ní riyadh saudi arabia jẹ́ òṣèrékùnrin ti ilẹ̀ saudi arabia ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ òṣèré ní ọdún 1984 ó sì gbajúgbajà fún ẹ̀dá-ìtàn tó máa ń kó nínú eré tash ma tash arabic طاش ما طاش ní ọdún 2012 nasser wà lára àwọn adájọ́ fún ètò orí ẹ̀rọ-a...
rory albanese rory scot albanese tí wọ́n bí ní may 29 1977 jẹ́ apanilẹ́rìn-ín òǹkọ̀wé ìtàn apanilẹ́rìn-ín àti olóòtú ètò lórí ẹ̀rọ-amóhùnmáwòrán ti orílẹ̀ èdè america
eddie albert edward albert heimberger tí wọ́n bí ní 22 1906 tó sì ṣaláìsí ní may 26 2005 jẹ́ òṣèrékùnrin àti onínúure ti orílẹ̀ èdè america
alan alda alan alda tí orúkọ àbísọ rẹ̀ ń jẹ́ alphonso joseph d'abruzzo tí wọ́n bí ní january 28 1936 jẹ́ òṣèrékùnrin apanilẹ́rìn-ín òǹkọ̀wé àti olùdarí eré ti orílẹ̀ èdè america
dave allen david tynan o'mahony 6 july 1936 10 march 2005 tí ọ̀pọ̀ ènìyàn dave allen jẹ́ apanilẹ́rìn-ín ti ilẹ̀ ireland àti òṣèrékùnrin
gracie allen grace ethel cecile rosalie allen july 26 1895 august 27 1964 fìgbà kan jẹ́ akọrin òṣèrébìnrin àti apanilẹ́rìn-ín tó di gbajumọ̀ lágbààyé látàrí iṣẹ́ rè pẹ̀lú george burns
marty allen morton david alpern march 23 1922 february 12 2018 tí ọ̀pọ̀ ènìyàn mọl sí marty allen jẹ́ apanilẹ́rìn-ín òṣèrékùnrin à ti onínúure ti orílẹ̀ èdè america ó ṣeré gẹ́gẹ́ bí i apanilẹ́rìn-ín ní ilé-ijó tí wọ́n sì máa ń pè é ní the darling of daytime tv
cristela alonzo cristela alonzo jẹ́ apanilẹ́rìn-ín òṣèrébìnrin òǹkọ̀wé àti aṣàgbéjáde eré tó ṣàfihàn nínú abc sitcom cristela èyí mu kó jẹ́ obìnrin àkọ́kọ́ láti mexico tó máa kọ́kọ́ ṣẹ̀dá ṣàgbéjáde àti kọ eré apanilẹ́rìn-ín kan
ọjà tejuosho tejuosho market jẹ́ ọjà gbajúgbajà kan ní ojuelegba-ọjú ọnà itire yaba ìpínlẹ̀ èkó ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà ọjà náà pín sí ọ̀nà méjì phase i and phase ii ó sì ní ọ̀pọ̀lọpò ohun àmúyẹ bí i iná omi ilé-oúnjẹ ilé-ìfowópamọ́ àyè láti gbọ́kọ̀ sí àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ ní ọdún díẹ̀ sẹ́yìn ijàm̀bá iná ba ọjà náà jẹ́ tí...
ìjígbé àwọ̀n ọmọ ilé ìwé chibok ní oru ọjọ́ kẹrìnlá sí kẹ̀ẹ́dọ́gún ọdún 2014 àwọn ìkọ̀ ogun boko haram jí àwọn ọmọ obìnrin ẹ̀rin dín ní ọ́rin-lé-nígba279 gbé ní government girls school ní ìlú chibok ìpínlẹ̀ bornu nàìjíríà ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ọmọ tí wọ́n jí gbé jẹ́ krìstẹ́nì kí ikọ̀ náà tó ya wo ilé ìwé náà wọ́n ti ti ilé ì...
yoruba people in the atlantic slave trade history of the yoruba tribes involvement in the atlantic slave trade àwọn ènìyàn yorùbá ṣe kó ipa púpọ̀ nínú àṣà àti ètò ọrọ̀-ajé nínú òwò ẹrú ti òwo ẹrú atilantiki láti ìgbà tí a lè sọ pé ó ti wà ní ọdún 1400 títí di 1900 ce ẹḿpáyà ọ̀yọ́ láti ọdún 1400 lọ ni aláyélúà ti ẹḿpáyà...
ìsìnrú gbèsè ìsìnrú gbèsè ni jíjẹ́ ẹ̀jẹ́ láti ṣiṣẹs fún èlò míràn án láti dógò fún gbèsè tí ènìyàn jẹ ẹlòmíràn èyí mú kí ẹni tí ó ya ìkejì lọ́wọ́ wà ní àkóso ẹnikejì títí di ìgbà tí ó ma rí owó náà ṣan the services required to repay the debt may be undefined and the services' duration may be undefined thus allowing the...
nínà àtẹ̀lẹsẹ̀ nínà àtẹ̀lẹsẹ̀ tàbí bastinado jẹ́ ọ̀nà láti fa ìrora tàbí yẹ̀yẹ́ nípa nína àtẹ̀lẹ̀sẹ̀ ẹlòmíràn pàápàá jù lọ ẹrú yàtò sí àwọn ọ̀nà míràn láti na ènìyàn nínà àtẹ̀lẹ̀sẹ̀ ma ń sábà fa ìrora ṣùgbọ́n kìí sábà ṣe ẹni tí wọ́n ń nà léṣe wọ́n ma ń sábà lo ẹgba tínrín bi pankẹ́rẹ́ àkọsílẹ̀ nípa nína àtẹ̀lẹ̀sẹ̀ tàbí...
karayuki-san àwọn obìnrin tí wón jì gbé laarin ṣẹ́ńtúrì kọkàndínlógún karayuki-san 唐行きさんjẹ́ orúkọ tí àwọn ará ilè japan tí wọn fún obìnrin tí wọn fí ipá jí gbé lọsí àwọn àgbègbè bí apá ìlà oòrùn asia siberia russian australia india láti lọ lò wọ́n gẹ́gẹ́ bí òsìsẹ̀ ìbálòpó láti yọ wọ́n kúrò nínú ìṣẹ́ láàrín ṣẹ́ńtúrì kọk...
ìjọba dahomey ìjọba dahomey jẹ́ ìjọba kan ní ìwọ̀ oòrùn áfíríkà tí orílẹ̀ èdè benin wà lọ́jọ́ òní ìjọba náà wà láti ọdún 1600 títí di 1904 wọ́n kó dahomey sí orí òkè abomey ìjọba náà di alágbára lágbègbè rẹ̀ ní àwọn ọdún 1700s wọ́n sì ségun àwọn ilẹ̀ tí ó wà ní gúúsù wọn láti tan ilẹ̀ wọn àwọn ilẹ̀ bi whydah ti ìjọba w...
bilal ibn rabah companion of muhammad and first islamic mu'azzin c580640 ojúewé yìí jẹ mọ́ nípa the companion of muhammad fún the mosque named in his honour ẹ wo rachel's tomb bilāl ibn rabāḥ lárúbáwá ‎ c 580640 jẹ́ ọ̀kan lára sàhabé tí ànọ́bì muhammad swt gbẹ́kẹ̀le tí ó sí fọkàntàn tí ànọ́bi náà sì jẹ́ ọ̀kan lára òjíṣ...
àwọn ẹ̀tọ́ ọmọ ènìyàn <templatestyles src=hlist/stylescss></templatestyles> <templatestyles src=hlist/stylescss></templatestyles> àwọn ẹ̀tọ́ ọmọ ènìyàn jẹ àwọn ìlànà àwọn ìwà tí ó tó sí ọmọ ènìyàn láti máa wù tí wọ́n sì ń dáàbòbò nígbàgbogbo ní àárín ara wa tàbí láàárín àgbègbè kan àti ní gbogbo ìlú kárí ayé wọ́n jẹ́ o...
ìkónilẹ́rú ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà traditional slave trade in southeastern nigeria ìkónilẹ́rú ti fi ara hàn ní gbogbo ọ̀nà káàkiri gbogbo ìtàn nàìjiríà ó fara hàn jùlọ ni àsìkò òwò-ẹrú atlantic àti òwò-ẹrú-saharan òwò-ẹrú tí di ohun tí ó lòdì sí òfin báyìí kárí-ayé àti ní orílè-èdè nìgéríà pàápàá ní orílè-èdè nàìjíríà à...
jihad ti usman dan fodio military conflict in nigeria and cameroon 18041808 jihad ti usman dan fodio jẹ ija ẹlẹsin-ologun to waye in orilẹ ede naijiria ati ilu cameroon ogun naa bẹrẹ nigba ti a lè usman dan fodiyo ogbon tarigi onimọ ẹsin islam ati olukọ kuro ni gobir eleyi ṣẹlẹ lati ọwọ ọkan ninu akẹẹkọ rẹ ọba yunfa us...
àwọn yorùbá tó ń ṣòwò ẹrú gba ojú omi atlantic history of the yoruba tribes involvement in the atlantic slave trade àwọn ẹ̀yà yorùbá kópa tó pọ̀ nínú okoòwò ẹrú ṣíṣe gba ojú omi atlantic pàápàá jù lọ nípa àṣà àti ètò-ọ̀rọ̀-ajé ní ọdún 1400 sí 1900 ce àwọn ìlú tí ọ̀yọ́ ń pàṣẹ lé bẹ̀rẹ̀ láti ọdún 1400 síwájú àwọn ìlú tí ...
ìsìnrú ní afíríkà nínú ìtàn ìsìnrú jẹ́ nǹkan tí ó gbajúmọ̀ ní ilẹ̀áfríkà bí ó ṣe gbajúmọ̀ ní àwọn apá míràn ní àgbáyé láyé àtijọ́ nígbà tí oko ẹrú trans-saharan oko ẹrú indian ocean àti oko ẹrú atlantic tí ó bẹ̀rẹ̀ ní àwọn ọdún 1500s bẹ̀rẹ̀ àwọn tí ó ń kọ́ni lẹ́rú tẹ́lẹ̀ ní áfíríkà bẹ̀rẹ̀ sí ń ta àwọn ẹrú fún àwọn oríl...
osu caste àṣà osu caste jẹ́ àṣà ní |ilẹ̀ ìgbò tí ó lòdì sí ìbádọ́rẹ́ àti fífẹ́ àwọn ènìyàn kan tí wọ́n ń pè ní osu nínú ìtàn àwọn osu jẹ́ ẹrú òrìṣà alusi ti àwọn igbo wọ́n gbàgbọ́ pé àwọn osu kìí ṣe ènìyàn pàtàkì bi nwadiala tàbí diala bí ó ti bẹ̀rẹ̀ wọ́n ti mọ àwọn kan bi osu láti ìgbà tí àwọn ilẹ̀ íbọ̀ ti wà lábé òfi...
bight ti biafra bight ti biafra atun ma n pe ni bight ti bonny ni órilẹ ede naijiria jẹ bight to wa ni ìwọ oòrùn aringbungbun etikun ilẹ́ afrika ni ila-oorun gulf ti orilẹ ede guinea àgbègbè bight ti biafra tabi mafra orukọ ilu mafra ni southern portugal larin capes formosa ati lopez jẹ ila-oorun ti gulf ti ilẹ guinea ...
ènìyàn gbígbé káàkiri gbígbé ènìyàn kiri jẹ́ ìṣòwò ti ènìyàn fún ìdí ti iṣẹ́-ipá líle iṣẹ́ ìfipábánilòpọ̀ ẹrú ìbálòpò tàbi ìlòkulò ìbálòpọ̀ fún ìṣòwò gbígbé ènìyàn kiri le wáyé láàárin orílẹ̀-èdè kan tàbí orílẹ̀-èdè méjì ó yàtọ̀ sí ti gbígbé ènìyàn wọ ìlú lọ́nà àlùmọ̀kọ́rọ́yí èyí tí ó jẹ́ àjọmọ̀ ẹni tí a gbé pẹ̀lú gbíg...
bight ti benin bight ti benin tabi bay ti benin ni bight to wa ni gulf ti guinea ni etikun iwọ oorun ti ilẹ afrika to gba órukọ rẹ̀ lati iṣẹdalẹ afin ti benin àgbègbè bight ti benin tọ kasi ila oorun fun kilometres ti oji le ni ẹ̀gbẹta 400 mi lati cape st paul lọsi nun outlet ti niger river lati ila oorun o tẹsi waju l...
àwọn àkókò tí wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí ní fòpin sí owo-eru àti iwofa fífòpin sí ẹrú kíkó wáyé lásìkò ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ni oríṣiríṣi orílẹ̀ èdè káàkiri àgbáyé ó bẹ̀rẹ̀ sí ní ṣẹlẹ̀ léraléra ní tẹ́lẹ̀ntẹ́lẹ̀ ní ìpele tí ó ju ọkàn lọ - fún àpẹẹrẹ fífòpin sí ẹrú kíkó wáyé ní àwọn àgbègbè kan gẹ́gẹ́ bí orílẹ̀ èdè bẹ́ẹ̀ náà ni àwọn ibòmíràn g...
ìsìnrú ní rómù àtijọ́ ìsìnrú ní róòmù àtijó kó ipa pàtàkì ní àwùjọ àti ètò ọrọ ajé róòmù yàtò sí lílò wọ́n láti ṣe iṣẹ́ agbára wọ́n lọ àwọn ẹrú fún ọ̀pọ̀ iṣẹ́ ilé àti fún àwọn iṣẹ́ ọpọlọ míràn àwọn tí ó ń ka owó àti àwọn oníṣègùn nígbà náà jẹ́ ẹrú àwọn ẹrú tí ó jẹ́ ọmọ orílẹ̀ èdè gríkì ma ń sábà jẹ́ alákọ̀wẹ́ àwọn tí k...
ẹrú kíkó ẹrú kíkó níṣe pẹ̀lú kí àwọn ológun kó àwọn ènìyàn kúrò ní agbègbè tí wọ́n ń gbé lọ sọ wọ́n di ẹrú ní ilẹ̀ ibòmíràn tẹ́lẹ̀ èyí jẹ́ ohun tó tọ́ tàbí tí ó jẹ mọ́ ogun jíjá ṣùgbọ́n lóde-òní ẹ̀ṣẹ̀ ni ó jẹ́ láti ìgbà ìwáṣẹ̀ ni ẹrú kíkó ti wà ní ilẹ̀ sumer tí a mọ̀ sí iraq lóde-òní ni àkọsílẹ̀ ẹrú kíkó ti wáyé jù lọ ...
ìbálòpò fún ẹ̀mí ìbálòpọ̀ fún ẹ̀mí túnmọ̀ sí kí ènìyàn ma ṣe iṣẹ́ aṣẹ́wó láti pèsè fún àwọn nǹkan àwọn àìní tí ó ṣe pàtàkì fún wọ́n ó túnmọ̀ sí kí àwọn tí kò nílé lórí tàbí àwọn tí ó kò ní ànfàní púpò láwùjọ ma lọ ìbálòpọ̀ gẹ́gẹ́ bí ọ̀nà láti pèsè fún oúnjẹ ibi tí wọ́n ma gbórílé àti àwọn míràn ìwọ́pọ̀ rẹ̀ ìbálòpọ̀ fún...
black lives matter black lives matter blm jẹ́ ìwọ́de ìjà àti ìṣọ̀rọ̀ lòdì sí ìṣẹlẹ́yàmẹ̀yà ìfìyàjẹ àti àwọn nǹkan míràn tí àwọn aláwọ̀ dúdú ń dójú kọ àwọn ohun tí ó ṣe pàtàkì nínú ìjà fún ètọ́ náà ni ìjà lòdì sí ìyà àìtó láti owó àwọn agbófinró bi ọlọ́pá àti ìfìyàjẹ àwọn aláwò dúdú ó bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú pípa trayvon martin mi...
triangular trade trade among three ports or regions triangular trade or triangle trade jẹ owo to waye lati igberiko mẹta tabi agbegbe triangular trade ma n ṣẹlẹ nigbati igberiko kan ba gbe ọja lọsi ibi ti wọn ti nilo rẹ ti eyi ṣi jẹ agbegbe ti wọn ti ma n gba ọja wọle eyi ni a ma fin ṣè ale kun ba awọn owo ti o ku ju ṣ...
oko ẹru ti adayeba oko ẹru ti adayeba tabi oko ẹru ti aristotelian jẹ ariyanjiyan lori óṣèlu aristotle to da loripe eniyan jẹ ẹru ni adayeba ṣugbọn awọn toku jẹ ẹru latari ofin tabi convention ọrọ ti aristotle sọ lóri oko ẹru aristotle ṣalaye pe ẹru adayeba jẹ ẹni ti o jẹ ọmọ gẹgẹbi adayeba ṣugbọn ẹlo mira lo ni o ṣe a...
etikun ti swahili coastal area of the indian ocean in southeast africa etikun ti swahili jẹ etikun ti ocean ti indian ni east africa ti awọn ẹya swahili ngbe eyi lekun pẹlu dar es salaam sofala ni mozambique mombasa gede pate island lamu and malindi ni kenya and kilwa ni tanzaniaóriṣiri coastal islands to wa ni swahili...
proslavery proslavery túmọ̀ sí fífi ọwọ́ sí ìsìnrú ìsìnrú jẹ́ ohùn tí àwọn ọ̀jọ̀gbọ́n àtijọ́ míràn fi owó sí ó sì jẹ́ ohun tí ó farahàn nínú ìwé mímọ́ àwọn ìwé àkọọ́lẹ̀ amẹ́ríkà àti britain àtijọ́ náà tún fọwọ́ sí ìsìnrú pàápàá jù lọ àwọn ìwé orílẹ̀ èdè amẹ́ríkà kí ìjà abẹ́lé orílẹ̀ èdè amẹ́ríkà ṣẹlẹ̀ àwọn kọ̀kan tí ó ...
ìsìnrú ní gríkì àtijọ́ ìsìnrú jẹ́ ohun tí ó wọ́pọ̀ gríkì láyé àtijó bí ó ti wọ́pọ̀ ní àwọn àwùjọ míràn nígbà náà àwọn iṣẹ́ tí wọ́n ń lọ àwọn ẹrú fún ni iṣẹ́ àgbẹ̀ iṣẹ́ kùsà àti gẹ́gẹ́ bi ọmọ ọ̀dọ̀ fún iṣẹ́ nínú ilé ní gríkì àtijọ́ wọn kò ka ẹrú mọ́ ara àwùjọ ṣùgbọ́n wọ́n rí wọn gẹ́gẹ́ bi ohun ìní ọ̀pọ̀ ẹrú kò lẹ́tọ́ lọ...
taiwo olowo olóyè daniel conrad taiwo tí a bí ní ọdún 1781 tí ó sì fi ayé sílẹ̀ ní ọjọ́ ogún oṣù kejì ọdún 1901 àwọn ènìyàn tún mọ̀ọ́ sí taiwo olówó ó jẹ́ olùtà ohun ìjà ogun olówó àwọn ẹrú afifúni àti olórí àdúgbò kan nígbà tí èkó wà lábé ìjọba britain ìpìlẹ̀ rẹ̀ a bí taiwo olowo ní ọdún 1781 ní isheri àdúgbò kan ní ì...
okoro idozuka okoro idozuka jẹ oludari ti 19th century ati jagun jagun ni agbegbe arondizuogu ilẹ naijiria arakunrin naa jẹ olujiroro agba si oludasilẹ abule ndiakunwanta uno arondizuogu okoro jẹ gbajumọ oniṣowo ẹru ṣiṣe to lowo lọwọ igbeèsi àye okoro idozuka ni a bisi agbegbe awka ṣugbọn ti o ko lọsi arondizuogu ni ce...
ologun kutere ologun kutere jẹ gẹ́gẹ́ bi oba èkó láti 1780s títí di ọdún 1803 òun ló jẹ́ lẹ́yìn oba eletu kekere ẹni tí ó wà lórí oyè láti ọdún sí 1775 and 1780 ologun kutere jẹ́ ọmọ erelu kuti ẹni tí ó jé ọmọ oba ado àti alaagba 'alagbigba' ẹni tí ó jẹ́ ọmọ ìjẹ̀sà àti olùbádámọ̀ràn oba akinsemoyin ìtàn rẹ̀ bàbá kutere...
niara bely niara bely c1790-1879 ti a mọ ni gbajumọ gẹgẹbi elizabeth bailey gomez jẹ olori ti luso-ilẹ afrika jẹ óniṣowo pataki ni century ti okan dinlogum arabinrin na jafafa lori owo oko ẹru ṣiṣe ni farenya ilẹ guinea itan igbesi àye niara niara bely jẹ ọmọbinrin emmanuel gomez oludari ti bakia ti luso-ilẹ afrika ni ...
n'gangue m'voumbe niambi n'gangue m'voumbe niambi jẹ́ ọba ìjọba loango ní àwọn ọdún tó gbẹ̀yìn ọdún 1600s ó rí ọ̀pọ̀ èrè nínú títa àwọn ènìyàn gẹ́gẹ́ bi ẹrú fún orílẹ̀ èdè kingdom of portugal|portugal gẹ́gẹ́ bí àkọsílẹ̀ olfert dapper niambi ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ ohun ìjà ogun bí ó tilẹ̀ jẹ́ wípé kò mọ bí a ṣe ń lò wọ́n
caty louette caty louette tabi cathy louet 1713-d lẹyin 1776 jẹ oniṣowo pataki ti ilẹ afrika caty jẹ ọkan lara awọn eniyan jakan ni agbegbe ti gorèe caty louette jẹ̀ ọmọbinrin arakunrin to wa lati ilẹ french nicolas louët to jẹ oṣiṣẹ ilẹ̀ french ti east india ati mistress rẹ caty de rufisque ti gorèe louette di signare...
fenda lawrence fenda lawrence 1742 lẹ́yìn 1780 jẹ́ olóko òwò ẹrú áfíríkà tí ó ṣiṣẹ́ yìí ní saloum ìlú kaur ìtàn ayé rẹ̀ fenda lawrence gbé lẹ́gbẹ̀ẹ́ odò gambia ní àwọn ọdún 1700s ní àdúgbò náà ó jé òlùbádúna dúrà láàrin àwọn oníṣòwò britain france àti àwọn oníṣòwò áfíríkà ó di ipò yìí mú lẹ́yìn ìgbà tí ó fẹ́ òyìnbó kan...
ìpalára ìpalára jẹ́ ìṣeni-láída búburú ní ara tí ó le ba ayé irú ẹni bẹ́ẹ̀ jẹ́ tàbí wíwà láyé irú ènìyàn bẹ́ẹ̀ a tún le ṣe àpèjúwe rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ìbanilára jẹ́ tí ó le dín iyì ohun kù bùrẹ́wà ohun bẹ́ẹ̀ àìlèṣe rẹ̀ tàbí kí ó sọ irú ohun bẹ́ẹ̀ di aláìpé ní ayé òde-òní èrò yìí túmọ̀ sí ohun tí ó burú jáì àká-ọ̀rọ̀ ní 2019 ...
akitoye akítóyè kú lọ́jọ́ kejì oṣù kẹsàn-án ọdún 1853 tí ọ̀pọ̀ ènìyàn máa ń ṣìpè nígbà mìíràn ní akíntóyè jẹ ọba eko ní ẹ̀mẹjì ó kọ́kọ́ jọba láti ọdún 1841 sí 1845 lẹ́yìn náà ó tún jọba láti ọdún 1851 sí 1853 bàbá rẹ̀ ni ọba ologun kutere àwọn àbúrò rẹ̀ sì ni àwọn ọba aládé ọṣìnlokùn àti àdèlé àjọsùn bí ó ṣe jọba wọ́n ...
ìpakúpa
atlantic slave trade slave trade 16th to 19th centuries ìsòwò ẹrú níatlantic tàbí transatlantic slave trade jẹ́ tàbí ìgbà tí àwọn oníṣòwò ẹrú bá gbé àwọn èèyàn aláwọ̀ dúdú kúrò gẹ́gẹ́ bí eru láti orílé áfíríkà lọsí amẹ́ríkà àwọn ará yúróòpù wọn á máa lo ọkọ̀ ojú omi ẹrú tí wọ́n fi ń ṣe òwò ẹrú máa ń lo ọ̀nà ìṣòwò onígu...
jumbes ti nkhotakota jumbes ti nkhotakota jẹ akojọpọ awọn oniṣowo ilẹ larubawa-swahili ti wọn gbe ni nkhotakota iwọ oorun ti ibudo ti malawi iṣẹ wọn ni ki wọn ma fi àṣọ gba ivory ati ẹru ni etikun ti swahili awọn óniṣowo yi lo gbe ẹsin musulumi ati àṣa rẹ̀ wa si agbegbe nikhotakota ti wọn si tun jẹ ẹni akọkọ lati gbin ...
emmanuel gomez agba emmanuel gomez jẹ ọmọ ilẹ luso-afrika to wa lati bissau to da dynasty ti luso-afrika silẹ ni bakia guinea ni century ti meji dinlógun arakunrin naa jẹ baba fun emmanuel gomez kekere ati niara bely
mary faber óniṣowo ẹru mary faber ni a tuma npe ni mary faber de sanger a bini c 1798 si freetown guinea-conakry to si ku lẹyin ọdun 1857 jẹ oniṣowo ẹru ilẹ afrika lati ọdun 1830s titi di ọdun 1852 arabinrin naa jẹ eniyan pataki ninu owo ẹru ṣise ti atlantic lati ilẹ guinea ati fun ija rẹ pẹlu roya navy ti ilẹ britisha...
antera duke antera duke wa ni aye titi di ẹyin ọdun 1788 jẹ óniṣowo ẹru ati oloye efik to wa lati calabar atijọ ni bight ti biafra ni ila oorun ti ilẹ naijiria agbegbe naa tidi ipinlẹ cross river nisin ni century meji dinlogun sẹyin antera yege to si di ọmọ ẹgbẹ awujọ ti ekpe eyi to ni ipa pupọ ninu owo ẹru ṣiṣe arakun...
osman digna sudanese ansar military commander 18361926 osman digna èdè larubawa عثمان دقنة c 1840 1926 jẹ olutẹle ilana ti muhammad ahmadẹni ti oun pe ara rẹ ni mahdi ni sudan jẹ oludari ologun nigba ogun ti mahdi gẹgẹbi ologun mahdi to pegede julọ osman kopa pataki ninu igbesi aye ọgagun charles george gordon ati ikun...
dame portugaise dame portugaise d lẹyin 1634 jẹ oniṣowo ẹru nhara ilẹ afrika arabinrin naa jẹ ọmọbinrin ọkunrin ilẹ portuguese ati arabinrin ilẹ afrika dame da oko owo ẹru silẹ ni rufisque nibi o ti jẹ alagata ti wọn maa n pe larin awọn oludari ilẹ portuguese ati afrika latari ẹya awọn obi rẹ̀ eyi jẹ ki dame dari owo ṣ...
aurelia correia dona aurelia correia d circa 1875 ti a tumọ si mae aurelia mame correia aurelia ati madame oralia jẹ̀ óniṣowo oko ẹru ti euro-ilẹ afrika igbesi àye aurelia aurelia jẹ eniyan pataki ninu owo ṣiṣe ti guinea-bissau ni century ti ọkan dinlogun arabinrin naa lo gbajumọ julọ ni agbègbè nhara ti wọn si wari fu...
francisca chiponda dona francisca josefa de moura meneses ni a tumọ si francisca chiponda jẹ ogboun tarigi ẹlẹya meji oniṣowo oko ẹru ti agbegbe tete ni portuguese mozambique to jẹ ọkan lara awọn to ṣe agba tẹru ina owo lati ilẹ mozambique de kazembe zambia nisin ni ọdun 1790 de 1798 lati kọja si ilẹ afrika lati ila oo...
betsy gbo betsy heard tí wọ́n bí ní1759 tí ó sì ṣaláìsí ní ọdún 1812 jẹ́ obìnrin oníṣòwò ẹrú àti oníṣòwò ará africa kan bàbá rẹ̀ jẹ́ oníṣòwò kan tó máa ń rin ìrìn àjò ní àwọn ọdún 1700 láti liverpool lọ england sí los islands èyí tó wá di guinea báyìí ìyá rẹ̀ jẹ́ ọmọ ilẹ̀ africa ó ṣeé ṣe kí bàbá rẹ̀ tẹ̀ lé àṣà ìbílẹ̀ è...
betsy heard betsy heard tí wọ́n bí ní1759 tí ó sì ṣaláìsí ní ọdún 1812 jẹ́ obìnrin oníṣòwò ẹrú àti oníṣòwò ará africa kan bàbá rẹ̀ jẹ́ oníṣòwò kan tó máa ń rin ìrìn àjò ní àwọn ọdún 1700 láti liverpool lọ england sí los islands èyí tó wá di guinea báyìí ìyá rẹ̀ jẹ́ ọmọ ilẹ̀ africa ó ṣeé ṣe kí bàbá rẹ̀ tẹ̀ lé àṣà ìbílẹ̀...
little ephraim robin john àti ancona robin john little ephraim robin john àti ancona robin robin john jọ jẹ́ àwọn oníṣòwò ẹrú ilẹ̀ afirika ní sẹ́ńtúrì kejìdínlógún tí wọ́n padà fún àwọn ẹrúkùnrin tí wọ́n jẹ́ ọmọ-ẹgbẹ́ ti old town calabur ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà ní òmìnira ọrundun 18th ẹrú nigbamii ati nikẹhin awọn ọkunr...
john cabess african merchant john cabess tí àwọn míràn ma ń kó bi john kabes tàbí john cabes c 1640s 1722 jẹ́ oníṣòwò ọmọ orílẹ̀ èdè áfíríkà tí ó gbajúmọ̀ nígbà ayé rẹ̀ ìlú komenda ara àwọn ìlú ìjọba eguafo ni ó ti ṣòwò ó jẹ́ ọ̀rẹ́ orílẹ̀ èdè britain ó sì ń ta ọjà fún ilé iṣẹ́ royal african company gẹ́gẹ́ bi oníṣòwò ó ...
victoria albis victoria albis d after 1777 jẹ́ obìnrin ọmọ senagal tí ó alágbára nítorí ó fẹ́ àwọn aláṣẹ àwọn òyìnbó tí ó sì jogún wọn ó wà lára àwọn gbajúmọ̀ obìnrin tí ó lágbára nítorí ó fẹ́ àwọn òyìnbó alágbára ní erékùṣù gorée láàárín àwọn elédè faransé senegal ó jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn gbajúmọ̀ alágbára obìnrin lásìkò...
akinsemoyin oba akinsemoyin jẹ́ oba èkó láti ọdún 1704 sí 1749 bàbá rẹ̀ ni oba ado àwọn ẹbí rẹ̀ sì ni erelu kuti àti oba gabaro ẹni tí ó jọba ṣáájú akinsemoyin gégé bí justice j o kassim ṣe fi léde ní ọjọ́ kàndínlógún oṣù kẹsàn-án ọdún 1978 ọmọ ọkùnrin mẹ́fà ni akinsemoyin ní orúkọ wọn ni sadeko amore/olukokun abisako ...
julia da silva cardoso julia da silva cardoso d after 1840 tí a tún mọ̀ sí mae julia ati na julia 'senhora julia' jẹ́ òyìnbó ọmọ ilẹ̀ adúláwọ̀ oníṣòwò ẹrú nhara ọmọ orílẹ̀ èdè portugal tí ó ń jẹ́ josé da silva cardoso ti cap verde ni ó tọ́ ọ dàgbà ó ṣe é ṣe kó jẹ́ ọmọ rẹ̀ ó fẹ́ ọmọ orílẹ̀ èdè portugal kan tí orúkọ rẹ̀ ...
kòsọ́kọ́ kòsọ́kọ́ ó wàjà ní 1872 ó jẹ́ ọmọ ilé oyè ológun kétere ó sì jẹ gẹ́gẹ́ bí i ọba ìlú èkó láti 1845 títí di 1851 ọba oṣìnlokùn ni bàbá rẹ̀ nígbà tí àwọn bàbá rẹ̀ ń ṣe ìdéwu ojúlarí tí ó jẹ́ bí ọba èkó láti 1829 títí di 1834/35 olúfúnmi ọdúnsì ládéga ògúnbámbí akínsànyà ogunjobi akimosa ìbíyẹmí adébánjọ matimoju ...
adele ajosun oba adele tàbí adele ajosun ó fi ayé sílẹ̀ ní ọdún 1837 jọba ní èkó fún ṣáà méjì àkọ́kọ́ láti ọdún c1811 sí 1821 àti ẹlẹ́kejì láti ọdún 1835 sí 1837 bàbá rẹ̀ ni oba ologun kutere àwọn ẹbí rẹ̀ sì ni oba osinlokun àti ọba akitoye ìran ologun kutere ti gun orí oyè ọba èkó fún ọ̀pọ̀ ìgbà láti ìgbà náà dídé ori...
chief kivoi mwendwa chief kivoi mwendwa tí wọ́n bí ní ọdún 1780 fìgbà kan jẹ́ oníṣòwò ọlọ́nà jínjìn tó ń gbé ní ìlú tí wọ́n ń pè ní kitui ní òde-òní kivoi gbajúmọ̀ jù lọ fún ṣíṣe amọ̀nà àwọn ajínhìnrere lọ sí ìlú kenya lẹ́yìn tó ṣamọ̀nà àwọn ajíhìnrere ti ilẹ̀ germany ìyẹn johann ludwig krapf àti johannes rebmann ti ìj...
ghezo ghezo tí sípẹ́lì rẹ̀ tún jẹ́ gezo jẹ́ ọba ilẹ̀ dahomey èyí tó ti di ìlú benin báyìí láti ọdụ́n1818 títí wọ 1859 ghezo rọ́pò ẹ̀gbọ́n rẹ̀ tí ń jẹ́ adandozan tó jọba láti ọdún 1797 títí wọ ọdún 1818 gẹ́gẹ́ bí i ọba látàri ìsọ̀tè tó wáyé pẹ̀lú ìànlọ́wọ́ àwọn olówò ẹrú ilẹ̀ brasil ìyẹn francisco félix de sousa ó jọba ...
sa'id ti egypt wāli of egypt and sudan 18221863 mohamed sa'id pasha ède larubawa محمد سعيد باشا èdè turkey mehmed said paşa ọjọ mẹta dinlogun óṣu march ọdun 1822 ọjọ mẹta dinlogunjanuary ọdun 1863 jẹ wāli ti egypt ati sudan lati ọdun 1854 de 1863 eyi ni to ri fealty ti arakunrin naa mi si ottoman sultan ṣugbọn pẹlu ómi...
people smuggling gbígbé èniyàn kúrò nínú ìlú kàn lọsí ibòmíràn lọnà èèrú
rosa de carvalho alvarenga rosa de carvalho alvarenga ni a tumọ si dona rosa de cacheu ati na rosa 'senhora rosa' 1780s d lẹ̀yin ọdun 1857 jẹ oniṣowo oko ẹru ti ilẹ euro-afrika itan igbèsi àye rosa rosa jẹ ọmọbinrin portuguese manuel de carvalho alvarenga lati cape verde ati pe iya rẹ jẹ ilẹ́ afrika ọmọ iya gomina fran...
human trafficking trade of humans for exploitation ìjínigbé káàkiri tí àwọn elédè gẹ̀ẹ́sì ń pè ní human trafficking jẹ́ ìfì ènìyàn ṣòwò fún ète iṣẹ́ àfipámúṣe ìfipápábánilò-ẹ̀ṣẹ̀ tàbí ìṣòwò ìfipábánilòpọ̀èyí lè wáyé tàbí ṣẹlẹ láàrín orílè èdè kàn ìlú kan tàbí agbègbè kan ìfípá jínigbé yatọ pátápátá sí gbígbé èniyàn lọ́...
abdallah of morocco sultan of morocco six times from 1729 to 1757 moulay abdallah 1694 títí di ọjọ́ kẹwàá oṣù kọkànlá ọdún 1757 lárúbáwá ‎ jẹ́ sultan orílẹ̀ èdè morocco lẹ́mẹfà láàrin 1729 sí 1757 ó gun orí ìtẹ́ ní àwọn ọdún 17291734 1736 17401741 17411742 17431747 àti 17481757 òun ni ọmọ sultan ismail ibn sharif ìtàn ...
ilé-iṣẹ́ senegal ilé-iṣẹ́ senegal tí kíkọ rẹ̀ ní èdè faranse jẹ́ compagnie du sénégal jẹ́ ilé-iṣẹ́ sẹ́ńtútì kẹtàdínológún ti ìlú faranse tó ń rí sí ìṣe àwọn agbègbè bí i saint-louis àti gorée island tó jẹ́ apá kan ilẹ̀ faranse ti senegal ilé-iṣẹ́ àkọ́kọ́ ilé-iṣẹ́ náà gbilẹ̀ sí àwọn agbègbè kan ní french west india comp...
ana joaquina dos santos e silva ana joaquina dos santos e silva 17881859 jẹ óniṣowo oko ẹru ti ilẹ euro-afrika ayanilowo ati agbẹ ti ilẹ angola arabinrin naa jẹ óniṣowo oko ẹru to tobi julọ ni angola nibi ti o tin ṣè oko owo pẹlu brazil ni ọdun 1830s to si na owo fun inawo ti joaquim rodrigues graça igbèsi àye ana ana ...
rasad rasad fl 1078 tí wọ́n tún máa ń pè ní sayyida rasad fìgbà kan jẹ́ obìnrin olóṣèlú ti ilẹ̀ egyptian caliph mother òun ni adelé fatimid egypt gẹ́gẹ́ bí i obìnrin olókìkí tó tún jẹ́ ìyá ọmọ rẹ̀ fatimid caliph al-mustansir billah láàárín ọdún 1044 wọ 1071 orúkọ yìí rasad túmọ̀ sí ìwòye
emina ilhamy wife of khedive tewfik pasha and walida pasha to her son abbas ii 1858-1931 emina ilhamy lárúbáwá ‎ ọjọ́ kẹrìnlẹ́lógún oṣù 1858 ọjọ́ kàn dínlógún oṣù kẹ́fà ọdún 1931 tí àwọn míràn mọ̀ sí amina ilhami jẹ́ ọmọbabìnrin ìjíptì àti ọmọ ìran muhammad ali dynasty òun ni khediva àkọ́kọ́ ní íjíptì láti 1879 títí di...
muhammad ali pasha muhammad ali pasha lárúbáwá ‎ tí a bí ní ọjọ́ kẹrin oṣù kẹta ọdún 1769 tí ó sì fi ayé sílẹ̀ ní ọjọ́ kejì oṣù kẹjọ ọdún 1849 jẹ́ gomina ottoman àti adarí orílẹ̀ èdè ìjíptì láàrin ọdún 1805 sí 1848 ọ̀pọ̀ káà mọ́ ara àwọn tí ó kọ́ íjíptì òde òní nígbà tí ìjọba rẹ̀ tàn ó dárí egypt sudan hejaz najd levan...
idris akọkọ ti morocco idris akọkọ ibn abd allah èdè larubawa إدريس بن عبد الله èdè roman idrīs ibn ʿabd allāh ni a tumọ si idris agba èdè larubawa إدريس الأكبر èdè roman idrīs al-akbar d 791 jẹ ara larubawa hasanid sharif ati oludari idrisid dynasty ti northern morocco pẹlu ajọṣèpọ ẹya berba ti awraba lẹyin ti wọn sa ...
idris keji ti morocco idris bin idris èdè larubawa إدريس بن إدريس ni a tumọsi idris keji èdè larubawa إدريس الثاني óṣu august ọdun 1791 óṣu august ọdun 1828 jẹ ọmọn was the son of idris akọkọ oludari idrisid dynasty ni morocco idris keji ni a bisi walīlī óṣu meji lẹ̀yin iku baba rẹ o dele baba rẹ ni ọdun 1803 igbesi ày...
oko ẹru ni etikun ti barbary oko ẹru ni etikun ti barbary owo oko ẹru ni etikun barbary jẹ iṣẹ labira ti kin ṣè ọfẹ to waye larin century ti mẹrin dinlogun ati meji dinlogun ni agbegbe etikun barbary ni apa ariwa ti ilẹ afrika ija ogun ti barbary gẹgẹbi iwadi robert davis ọpọlọpọ awọn ara ilẹ europe ni awọn ole abẹ omi...
etikun ti oko ẹru ti iwọ oorun ilẹ afrika historical name of region in west africa etikun oko ẹru yi jẹ oruko adayeba ti a ti lo tẹ̀lẹri fun apa etikun iwọ oorun ni agbegbe bight ti biafra ati bight ti benin to wa ni arin odo volta ati lagoon ti ekoórukọ yi ni a yọ latari itan agbegbe naa gẹgẹbi ọna kan gbogi ti awọn ẹ...
etikun ti barbary coastal region of north africa inhabited by berber people etikun ti barbary a tun mọ si barbary berbery tabi etikun ti berber jẹ orukọ ta fun agbegbe etikun ti ariwa ilẹ afrika tabi mahhreb papa julọ ibudo ottoman pẹlu rẹ ni adele to wa ni algiers tripoli beylik ti tunis ati sultanata ti morroco lati ...
ija ikonilẹru ti suðuroy barbary slave raids against the faroe islands ija ikonilẹru ti suðuroy jẹ́ ija ti awọn afigba ọkọ oju omi lai ariwaiwọ oorun ilẹ́ afrika to ṣẹlẹ ni suðuroy ni erekusu faroe ni summer ti ọdun 1629 eyi lo jasi ijinigbe awọn eniyan ọgbon ti wọn obinrin ati ọmọde ti wọn kogbe ni etikun ti barbary t...
turkish abductions barbary slave raids against iceland turkish abductions tí ó túmọ̀ sí àwọn ìjínigbé ní orílẹ̀ èdè turkey-àgbègbè mediterranean nígbà náà jẹ́ oríṣi ìkónilẹ́rú tí àwọn jàndùkú ojú omi láti àríwá ìwọ̀ oòrùn áfíríkà ṣe ní orílẹ̀ èdè iceland ní ìgbà oru ọdún 1627 àwọn jàndùkú ojú omi náà wá láti ìlú algier...
ismail ibn sharif moulay ismail ibn sharif lárúbáwá ‎ tí a bí ní 1645 ní sijilmassa tí ó sì fi ayé sílẹ̀ ní ọjọ́ kejìlélógún oṣù kẹta oṣù 1727 ní meknes jẹ́ sultan morocco láti ọdún 1672 sí 1727 gẹ́gẹ́ bi adarí kejì 'alawi dynasty òun ni ọmọkùnrin keje moulay sharif ó sì fi ìgbà kan jẹ́ gómìnà àgbègbè fez àti àríwá mor...
ọkọ ẹrú barbary oko ẹrú barbary jẹ́ àwọn ọjà ẹrú tí ó wà ní àwọn ìpínlẹ̀ barbary àwọn jàndùkú odò tí ó jẹ́ ọmọ barbary ya wọ àwọn ọkọ̀ ojú omi ìlú ẹgbẹ́ odò láti italy dé netherland ireland àti gúúsù apá ìwọ̀ oòrùn britain títí dé àríwá iceland àti ìlà-oòrùn mediterra apá ìlà-oòrùn mediterranean ottoman ni ìṣẹ̀lẹ̀ yí w...
john ezzidio john ezzidio c 1810 october 1872 jẹ́ ẹrú nupe tí ó gba òmìnira tí ó sì padà di oníṣòwò àti olóṣèlú ńlá ní orílẹ̀ èdè sierra leone wọ́n tu sílẹ̀ nínú ọkọ̀ ẹrú tí ó ń lọ sí orílẹ̀ èdè brazil ó kọ́ iṣẹ́ lábé ọmọ orílẹ̀ èdè faransé kan ẹni tí ó kọ bí a ṣe ń kọ àti kàwé ezzidio padà dé ipò mayor ìlú freetown ó ...
john jea john jea 1773 lẹ́yìn 1817 jẹ́ ònkọ̀wé oníwàásù àti awakọ̀ ojú omi ọmọ orílẹ̀ èdè amẹ́ríkà mọ́ áfíríkà ó gbajúmọ̀ fún ìwé rẹ̀ tí ó kọ ní ọdún 1811 the life history and unparalleled sufferings of john jea the african preacher jea di ẹrú láti ìgbà tí ó sì jẹ́ èwe lẹ́yìn ìgbà tí ó sì gbòminira ní 1790s ó bẹ̀rẹ̀ sí...
s'nabou african interpreter alima s'nabou tí a bí ní ọdún 1880 jẹ́ atúmọ̀ èdè tí ó wá láti ibi tí nàìjíríà wà lónìí tí ó tẹ́lèé arìnrìn-àjò faransé kan tí orúkọ rẹ̀ jẹ́ lieutenant mizon ìtàn rẹ̀ a bí alima s'nabou sínú ìdílé olóyè konanki nínú ìlú igbobé lẹ́gbẹ̀ẹ́ lokoja níbi tí odò benue àti niger ti pàdé ó gbó èdè fa...
oshodi tapa chief oshodi landuji tapa c 1800 1868 jẹ́ balógun oba kosoko àti ara àwọn olóyè tí ó lágbára jù lọ ní ààfin oba èkó ìpìlẹ̀ rẹ̀ ọ̀pọ̀ gbàgbọ́ pé oshodi tapa wá láti ẹ̀yà nupe ní bida tí ó wà lábé oba osinlokun ìdílé oshodi sọ wípé nígbà tí tapa jẹ́ ọmọdé àwọn olóko ẹrú pinu láti gbe sínú ọkọ omi portugal tí ...
selim aga sudanese writer and critic 18261875 selim aga c 1826 tí ó sì fi ayé sílẹ̀ ní ọdún 1875 jẹ́ ọmọ orílẹ̀ èdè sudan kan tí àwọn olókowò ẹrú arab jígbé nígbà tí ó jẹ́ ọmọ ọdún mẹ́jọ tí wọ́n sì mú wá sí scotland ní ọdún 1836 níbi tí wọ́n ti tọ dàgbà gẹ́gẹ́ bi ọkùnrin llómìnira selim kọ ìwé nípa ayé rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi ẹr...
simon deng simon aban deng jẹ́ ajàfẹ́tọ́ ènìyàn ọmọ orílẹ̀ èdè sudan tí united states wọ́n jí simon gbé nígbà tí ó wà ní èwe ó jẹ́ ọmọ bíbí ìjọba shilluk ní gúúsù sudan deng lọ ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọdún gẹ́gẹ́ bi ẹrú ní gúúsù sudan ìtàn wọ́n kó simon lẹ́rú nígbà tí ó jẹ́ ọmọ ọdún mẹ́sàn nígbà tí aládùúgbò rẹ̀ kan sọ pé kó tẹ̀lẹ́...
trans sahara trade ìṣòwò láàrín àwọn èèyàn ilé afíríkà àti mediterranean trans-saharan trade tàbí ìṣòwò láàrín sahara nílò ìrìn-àjò kọjá sahara láàrín ìwọ̀-oòrùn central ìlà-orùn àti àríwá áfíríkà lákòkò tí ó ti ń wà lati àwọn àkókó tí wọ́n pè ní prehistoric times àwọn àkókó ìṣààjúu èyí tí ó jẹ́ ìgbà kàn ti iṣowo gbòòr...
charlesi kẹta
charlesì kẹta charles iii charles philip arthur george ti a bi 14 november 1948 jẹ ọba ti ilẹ̀ọba aṣọ̀kan ati 14 miiran commonwealth ijọba
william alade ti wales william alade ti wales william arthur philip louis tí a bí 21 june 1982 ni ajogún gbangba si itẹ britani oun ni ọmọ agba ti charles iii ati diana ọmọ-binrin ọba ti wales
g33 awọn orilẹ-ede to sese le g33 tabi ọja pataki awọn ọrẹ ti ogbin
g8