language string | goal string | solution0 string | solution1 string | label int64 |
|---|---|---|---|---|
Yoruba | Báwo ni mo ṣe le kó erè oko bíi ọsàn àti àgbàdo dé ilé láti oko? | Mo lè lo apẹ̀rẹ̀ | Mo lè lo aṣọ ìbora | 0 |
Yoruba | Ìka wo ni wọ́n maá ń fi òrùka ìgbéyàwó sí? | òrùká yẹmí ní ọwọ́ òsì | òrùká yẹmí ní ọwọ́ ọ̀tún | 0 |
Yoruba | Kíni a fi ń d́á iná àsè | igi tó gbẹ la fi maá n dá iná àsè | ewé tútù la fi maá n dá iná àsè | 0 |
Yoruba | kíni ìyá má fi ń gbé ọmọ pọ́n? | ìró àti okùn ni ìyá fi ń gbé ọmọ pọ́n | iro ati ọjà ni ìyá má fi ń gbé ọmọ pọ́n | 1 |
Yoruba | Kíni a fi ń da ẹja lójú kó má bà tete bájẹ | Ata la fi ń da ẹja lójú kó má bà tete bájẹ | Iyọ̀ la fi ń da ẹja lójú kó má bà tete bájẹ | 1 |
Yoruba | ọ̀nà tó tọ́ wo la maá ń gbà kí asọ fi gbẹ? | fún asọ daádaa kí o sá sí òrùn | fún asọ daádaa kí o sá sí inú ilé | 0 |
Yoruba | Kíni àwọn àgbẹ̀ fi maá ń kó ewé tàbí koríko papọ̀? | wón maá ń lo ọkọ́ fi kó ewé tàbí koríko papọ̀ | wón maá ń lo réèkì fi kó ewé tàbí koríko papọ̀ | 1 |
Yoruba | Ọ̀nà wo la fí maá ń gba omi òjò | gbígbé igbá sí abẹ́ òrùlé | gbígbé apẹ̀rẹ̀ sí abẹ́ òrùlé | 0 |
Yoruba | Tí o bá fẹ́ se ìlu bàtá tí́ o dára, irú igi wo ni ó yẹ kí o lò ́ | Igi líle bi mahogany tàbí ìrókò ni a fí ń se ìlu bàtá tí ó dára | Igi rírọ̀ bi pine tàbí́ balsa ni a fí ń se ì̀lu bàtá tí ó dára | 0 |
Yoruba | Ni ìlu bàtá, èwo ni ótobi jùlọ? | Ìyá ìlù ni ó tóbi jùlọ nínu àwọn ìlu bàtá | ọ̀mélé ni ó tóbi jùlọ nínú àwọn ìlu bàtá | 0 |
Yoruba | kíni a maá ń fi sé àdirẹ | a maá ń fi asọ àti ọsẹ sé àdirẹ | a maá ń fi asọ àti aró sé àdirẹ | 1 |
Yoruba | kíni ó yẹ ká fi sí ewédú kó lè yọ̀ fùn jìjà daádaa? | o yẹ ká fi kán-ún sí i | o yẹ ká fi epo pupa sí i | 0 |
Yoruba | Iru ilẹ̀ wo lo dára jùlọ fún kíkó ilé tó maa duro pẹ́? | ilẹ̀ amọ̀ ni a le fi kọ iru ile bẹ́ẹ̀ | iyẹ̀pẹ̀ iyanrìn ni a le fi kọ iru ile bẹ́ẹ̀ | 0 |
Yoruba | Kí ni a maá ń fi sí àdìrẹ ̀abí ànkárá ta báa ń fọ̀ kí àwọ̀ rè má bà tètè parẹ́ | a máa ń fi iyọ̀ sí ànkárá àti àdìrẹ ta báa ń fọọ kí àwọ̀ rè má báa tètè parẹ́ | a máa ń fi kikan sí ànkárá àti àdìrẹ ta báa ń fọọ kí àwọ̀ rè má bàa tètè parẹ́ | 0 |
Yoruba | Kí ló máa ń ṣẹlẹ̀ sí àsìá tí afẹ́fẹ́ bá fẹ́ lágbára? | ó máa n mì tàbí kí ó fẹ́rẹ̀ẹ́ já láti ara igi | ó máa n dúró ṣinṣin, kò sì ní mì rárá | 0 |
Yoruba | Níbo ni àsìá máa ń kọ sí nígbà tí afẹ́fẹ́ ń fẹ́? | Àsìá máa ń kọ sí ibi tí afẹ́fẹ́ ń lọ sí | Àsìá máa ń kọ sí ibi tí afẹ́fẹ́ ti wá. | 0 |
Yoruba | Kí ló máa ń ṣẹlẹ̀ sí omi tí a bá fi sínú ẹ̀rọ amóhuntutù? | Omi náà yóò di yìnyín | Omi náà yóò di gbígbóná | 0 |
Yoruba | kíni ó yẹ kí ènìyaǹ fi wé ọrùn rẹ ní ìgbà òtútù? | aṣọ ìnujú | aṣọ òkè/ aṣọ ìborùn | 1 |
Yoruba | kíni ohun tó dára jùlọ lati fi lẹ àwo tó fọ́ sí méjì? | lẹ àwo náà pọ̀ pẹ̀lú èedú | lẹ àwo náà pọ̀ pẹ̀lú òǹlẹ̀ | 1 |
Yoruba | láti fọ aṣọ tó dọ̀tí | mo lè lo ọṣẹ Ìfọṣọ | mo lè lo aró | 0 |
Yoruba | O fẹ́ ṣe ibi ìsáṣọsi ní ẹ̀yìnkùnlé rẹ, kíni ohun elo tó dáa jùlọ? | Na okùn gígùn kan láàrín ọ̀pá méjì, kí o sì só ṣinṣin. | Na òwú gígùn kan láàrín ọ̀pá méjì, kí o sì só ṣinṣin. | 0 |
Yoruba | Tí o ba fẹ́ ọ̀bẹ tí ó mú, kíni ó yẹ kí o ṣe | lo òkuta láti fi pọ́n ẹnu ọ̀bẹ náà | lo páálí láti fi pọ́n ẹnu ọ̀bẹ náà | 0 |
Yoruba | Tí a bá fẹ́ ya irun ọmọ kékeré | ó dára kí a farabalẹ̀ ya irun na pẹ̀lú àmúga. | ó dára kí a farabalẹ̀ ya irun na pẹ̀lú òǹyà | 1 |
Yoruba | Láti dín dídán ojú re kù ṣáaju yìya foto, ó da kí o | fi èérú pa ojú àti ẹkẹ́ rẹ fẹ́rẹ́fẹ́ | fi àtíkè pa ojú àti ẹkẹ́ rẹ fẹ́rẹ́fẹ́ | 1 |
Yoruba | Lẹ́yìn tí o bá lò ọ̀bẹ ní ilé ìdáná, kí ni ó yẹ kí o ṣe? | fọ̀ ọ́ lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀ kí o sì fi sí ilẹ̀ | fọ̀ ọ́ lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀ kí o sì fi pamọ́ | 1 |
Yoruba | Àwọn èròjà tí a lè fi sínu ewédú ni | káún, iyọ̀, irú | káún, iyọ̀, aró | 0 |
Yoruba | Láti fọ ọwọ́ rẹ lẹ́yìn tí o bá dáná tán | fi ọṣẹ ra ọwọ́ rẹ, kí o sì fi omi tí ó mọ́ saǹ-án | fi àtíke ra ọwọ́ rẹ, kí o sì fi omi tí ó mọ́ saǹ-án | 0 |
Yoruba | Láti tukọ̀ ọkọ̀ ojú omi kékeré | a lè lo òbèlè | a lè lo ọ̀pá | 0 |
Yoruba | Ọ̀nà wo ló dára jù láti kọ́ ọmọdé láti ya òbìrìkìtì? | lo ìderí ìgò róbótó láti fi tọ sọ́nà | lo ìderí ìgò onígun mẹrin láti fi tọ sọ́nà | 0 |
Yoruba | Nígbà tí ènìà bá fẹ́ kun ilé, ó dáa láti | tẹ́ ìwé ìròyìn sí abẹ́ ibi tí ó fẹ́ kun | tẹ́ ìwé ìfúniláyè sí abẹ́ ibi tí ó fẹ́ kun | 0 |
Yoruba | Láti fọ àwọn aṣọ ìbora tí ó dọ̀tí, | kó wọn sínu ẹ̀rọ ìfọṣọ, kí o da ọṣẹ àti omi sì i, kí o sì tanná si. | kó wọn sínu ẹ̀rọ ìlọta, kí o da ọṣẹ àti omi sì i, kí o sì tanná si. | 0 |
Yoruba | Kíni ohun tí a tún lè fi pọ́n ẹ̀bà nígbà tí kò bá sí ìgbákọ? | a lè lo fìlà | a lè lo síbí | 1 |
Yoruba | Nígbà to bá tan ẹ̀rọ amúlétutù, ó yẹ kí o | sí gbogbo fèrèsé àti ilẹ̀kùn | ti gbogbo fèrèsé àti ilẹ̀kùn | 1 |
Yoruba | Kíni ohun tí ó tọ́ láti ṣe tí ago ọwọ́ rẹ kò bá ṣiṣẹ́? | Mú bátìrì àtijọ́ jáde kí o fì bátìrì tuntun síi. | Mú bátìrì àtijọ́ jáde kí o fì bọ́tìnì tuntun síi. | 0 |
Yoruba | kíni ó yẹ kí́ o ṣe lẹ́yìn tí o ba lo ẹ̀ro agbálẹ? | pa á, kí o sì tọju rẹ̀ sí ibi tí ó pamọ́ | pa á, kí o sì tọju rẹ̀ sí ibi tí ó ṣí sílẹ̀ | 0 |
Yoruba | àgbétẹ́lẹ̀ tí o dára ju nígbà tí à bá fẹ́ lo ẹ̀rọ agbáwòrányọ ni | ògiri funfun kan | ògiri dúdú kan | 0 |
Yoruba | agbóhùnsáfẹ́fẹ́ rẹ ko ṣiṣẹ́, kíni kí o kọ́kọ́ ṣe? | ríi dájú pé bọ́tìnì agbára tí wà ní títàn | ríi dájú pé bọ́tìnì ìdádúró tí wà ní títàn | 0 |
Yoruba | Kíni a lè fi rán ṣòkòtò tí o ya? | Abẹ́ẹ́rẹ́ àti òwú | Abẹ́ẹ́rẹ́ àti okùn | 0 |
Yoruba | Kíni ohun èlò tí ó dára jùlọ láti rẹ́ ata rodo? | àdá tí ó mú daadaa | ọ̀bẹ tí ó mú daadaa | 1 |
Yoruba | Tí mo bá fẹ mọ̀ bí iṣú bá tí jiná, | mo ma fi àmúga ṣàyẹ̀wò bóyá ó ti rọ̀ | mo ma mi ìkòkò lati wò bóyá ó ti rọ̀ | 0 |
Yoruba | Tí ọ̀nà ọ̀fun rẹ bá n dun ọ, kí ni o lè ṣe? | po omi gbọ́na pèlú oyin àti òrònbó kíkan, kí o sì mu ú | po omi gbọ́na pèlú àádùn àti òrònbó kíkan, kí o sì mu ú | 0 |
Yoruba | Ẹ̀yà ara wo ni ko yẹ kí o fi ọwọ́ kan lẹ́yìn ti o ba lọ/rẹ́ ata? | kò yẹ kí o fọwọ́kan ojú rẹ | kò yẹ kí o fọwọ́kan ọwọ́ rẹ | 0 |
Yoruba | Kíni o lè lo rọ́pọ̀ ọmọ ayò nígba tí o bá ń tá ayò ọlọ́pọ́n | Lo àwọn òkuta wẹ́wẹ́ | Lo àwọn òkuta tí o tóbi | 0 |
Yoruba | Kini ọna ailewu lati bọ́ lẹ̀ kuro ninu ọkọ òfurufú lẹ́hìn tí o bá balẹ̀? | Dìde lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀, gbé àpò rẹ, kí o si sáré jade | Ṣe sùúrù, kí o si rọra tèlé ìlànà | 1 |
Yoruba | Tí ìṣó ba n yọ lára tabili rẹ, | fi ìkànṣo lù ú padà sínu tabili | fi ṣíbí lù ú padà sínu tabili | 0 |
Yoruba | O ṣèṣẹ fọ aṣọ ibọsẹ re, o sì fẹ́ kí ó tètè gbẹ | sá a sí óòrun titi yóò fi gbẹ. | fi sínu àpò ilé-ìwé rẹ titi yóò fi gbẹ. | 0 |
Yoruba | O fẹ lo agbóhùnsáfẹ́fẹ́ rẹ ni ita láì dàmú àwọn aladugbo | Dín ìwọ̀n dídún si ipele kékeré | Dín ìwọ̀n dídún si ipele gíga | 0 |
Yoruba | Ọ̀pá omi kan ń jò ní ilé ìdana rẹ | fi tìmùtìmù dí ibi ti ó ń jò náà | fi téèpù wé ibi ti ó ń jò náà | 1 |
Yoruba | Kíni ọ̀nà tí ó dára jùlọ láti gbé ibùsùn ti o wúwo | gbé sókè pẹ̀lú ìrànlọ́wọ́ ẹlòmíràn | gbé sókè pẹ̀lú ìrànlọ́wọ́ igi ìgbálẹ̀ | 0 |
Yoruba | Ḱíni ó yẹ kí o ṣe lẹyìn tí o bá gé àlùbọ́sà? | fọ ọwọ́ rẹ pẹ̀lú ọṣẹ àti omi | fọ ọwọ́ rẹ pẹ̀lú epo àti omi | 0 |
Yoruba | O fẹ́ tọ́ju oúnjẹ sínu ẹ̀rọ amóhuntutù | jẹ́ kí oúnjẹ náà tutù kí o tó fi sínu ẹ̀rọ amóhuntutù | fi oúnjẹ gbígbóná tààrà sínu ẹ̀rọ amóhuntutù | 0 |
Yoruba | Lati wọn ìyẹ̀fun tí o tọ́ fun àkàrà òyínbó | lo òǹwọ̀n lati wọn ìyẹ̀fùn tí ó péye | lo okùn ìwọnṣọ lati wọn ìyẹ̀fùn tí ó péye | 0 |
Yoruba | Kí ni ọ̀nà tó dára jù lati mọ̀ bí epo ba ti gbóna tó nígbà to bá ń dín àkàrà | bu omi díẹ̀ sínu epo | bu àkàrà díẹ̀ sìnu epo | 1 |
Yoruba | Irú aṣọ wo ni o yẹ lati fi nu àwo oju rẹ | Aṣo ìnulẹ̀ | Aṣọ ìnujú | 1 |
Yoruba | Lati mo bii ẹ̀rọ ìlọṣọ ba ti gbona to fún lílò | Gbé ojú ẹ̀ro náà sí orí aṣọ díẹ̀ lati fi dán-an wò | Gbé ojú ẹ̀ro náà sí àtẹlẹwọ rẹ lati fi dán-an wò | 0 |
Yoruba | Ò fẹ gbin àgbado ni ẹ̀yìnkunlé rẹ, ohun èlò wo ni ó dára ju lati fi wa ihò? | Lo ọkọ́ lati fi walẹ̀ | lo ìderí ìgò lati fi walẹ̀ | 0 |
Yoruba | Bawo ni o ṣe lè nu ẹrẹ̀ kúrò lára bàtà rẹ? | fi omi ṣan ẹrẹ̀ naa kuro | fi ọwọ nu ẹrẹ̀ náà kurò | 0 |
Yoruba | Lati se ẹyin, èwo nínú àwọn ìgbésẹ̀ wọ̀nyí ni ó yẹ kí o tẹ̀le? | fi ẹyin sínu omi, gbé e ka ná, sì jẹ́ kí o se fun bi ìṣẹjú mẹ́wàá | fi ẹyin sínu òroró, gbé e ka ná, sì jẹ́ kí o se fun bi ìṣẹjú mẹ́wàá | 0 |
Yoruba | Ki ni o le ṣe nígbà tí ìdọ̀tí bá kó sí ọ ní ojú? | mo lè̀ fi ọwọ́ mímọ́ gbo ojú mi | mo lè̀ fi omi mímọ́ ṣan ojú mi | 1 |
Yoruba | Lati di ṣíbí mu, ó yẹ kí n | lo ọwọ́ mi | lo ẹsẹ̀ mi | 0 |
Yoruba | Tí o ba fẹ́ gún iyán, kíni ó yẹ kí o kọ́kọ́ ṣe? | Bẹ iṣu náà kí o sì sè é | Bẹ iṣu náà kí o sì gun láì sè é | 0 |
Yoruba | Láti lè mọ̀ bóyá ìbẹ́pẹ ti pọ́n? | Rọra tẹ awọ ara ìbẹ́pe náà | Rọra fi ìṣó gún ìbẹ́pẹ náà | 0 |
Yoruba | Tí o ba fẹ́ jẹ ìbẹ́pẹ, kíni ó yẹ kí o kọ́kọ́ ṣe? | Fí omi ṣan ìbẹ́pẹ náà kí o tó jẹ | Fi aṣọ nu ìbẹ́pẹ náà kí o tó jẹ | 0 |
Yoruba | kí ni o le ṣe lati jẹ́ kí òórùn ẹja kúrò ní ọwọ́ rẹ? | fí epo ra ọwọ́ rẹ, kí o sì sàn-án | fí ọsàn wẹ́wẹ́ ra ọwọ́ rẹ, kí o sì sàn-án | 1 |
Yoruba | Mo lè fi omi àgbọn | fọ aṣọ ìbora mi | se ìrẹsì alagbọn | 1 |
Yoruba | Kí ni o le ṣe lati jẹ ki ọ̀gẹ̀dè dòdò pọ́n kíákíá? | tọ́jú rẹ sí inú ẹ̀rọ amóhuntutù mọ́jú | tọ́jú rẹ sí ibi tí ó mú ooru mọ́jú | 1 |
Yoruba | Lára àwọn èròjà fún ọ̀lẹ̀lẹ̀ ni? | ẹ̀wà, ata, iyọ, epo pupa, edé | ẹ̀wà, ata, iyọ, kaúń, edé | 0 |
Yoruba | Bawo ni o ṣe lè fo ònà lailewu? | Wò bi ọkọ̀ ba n bọ kí o to fònà | Di ojú rẹ kí o to fònà | 0 |
Yoruba | Ibo ni o lè tọ́jú ago ọwọ́ rẹ sí? | Inu ìkòkò ìdáná | Obì ni ó dára jùlọ ní èròjà | 1 |
Yoruba | Nígbà tí a bá fẹ́ ṣe ọbẹ̀ olú, | Olú ni ó dára jùlọ ní èròjà | null | 0 |
Yoruba | Tí a bá fẹ́ rí àwọn èèrà salámọ́ | Inú yìnyín dìdì ni a máa wò | Inú òkìtì ọ̀gán ni a máa wò | 1 |
Yoruba | Ilẹ̀kùn ilé tí a fi àgádágodo tì pa | Ìṣó ni ó lè sí i pẹ̀lú ìrọ̀rùn | Kọ́kọ́rọ́ ni ó lè sí i pẹ̀lú ìrọ̀rùn | 1 |
Yoruba | Kí ni mo lè fi ti ilẹ̀kùn ilé mi pa? | Kọ́kọ́rọ́ ni mo lè lo láti ti ilẹ̀kùn mi pa | Àgádágodo ni mo le lò láti fi ti ilẹ̀kùn mi pa. | 1 |
Yoruba | Kí ni àwọn ọmọ òkú máa ń jẹ́ lẹ́yìn ikú òbí wọn? | Ogún ni àwọn ọmọ òkú máa ń jẹ́ | Àmàlà ni àwọn ọmọ òkú máa ń jẹ | 0 |
Yoruba | Tí ará mi kò bá yá, kí ni mo ma lò? | Oúnjẹ ní mo ma lò | Ògùn ni mo ma lò | 1 |
Yoruba | Tí omi ìrẹ̀sí kò bá gbẹ́ ní orí iná | A máa da ìrẹsì sínú àpò láti sẹ́ ẹ | A máa da ìrẹsì sínú asẹ́ láti ṣẹ́ ẹ | 1 |
Yoruba | Kí ni nǹkan tí ènìyàn máa wò láti rí ara rẹ̀ nígbà tí ó bá múra tán? | Dígí ni ènìyàn máa wò | Ògiri ni ènìyàn máa wò | 0 |
Yoruba | Láti pèsè Àmàlà fún oúnjẹ | A nílò ọmọrogùn | A nílò ìjábẹ̀ | 0 |
Yoruba | Níbo ni àyè tí ó wà láàárín apá sí èjìká? | Ọrùn-ọwọ́ ni àyè tí ó wà láàárín apá sí èjìká | Ìgùnpá ni àyè tí ó wà láàárín apá sí èjìká | 1 |
Yoruba | Nígbà tí mo bá fẹ́ kọ lẹ́tà, kí ni mo ma lò? | Gègé ni mo máa lò láti kọ lẹ́tà | Ẹfun ni mo máa lò láti kọ lẹ́tà | 0 |
Yoruba | Irú ilé wo ni a kọ́ sórí ara wọn? | Ahéré ni ilé tí a kọ sórí ara wọn | Ilé-alájà tàbí pẹ̀tẹsì ni ilé tí a kọ́ sórí ara wọn | 1 |
Yoruba | Tí mo bá fẹ́ dìbò, ìka wo ni màá lò? | Àtàǹpàkò ni ìka tí ó yẹ láti dìbò | Ìka àárín ni ó yẹ láti dìbò | 0 |
Yoruba | Nígbà tí òrùlé ilé mi bá ń jò | Màá gun igi láti lọ yẹ̀ ẹ́ wò | Màá gun àtẹ̀gùn láti lọ yẹ̀ ẹ́ wò | 1 |
Yoruba | Tí ọtí bá ń wù ẹ́ mu | Lo igbá láti mú ọtí | Lo apẹ̀rẹ̀ láti mu ọtí | 0 |
Yoruba | Àwọn alábàárù tí kò bá lo abọ́ láti ko ẹrù | Wọ́n máa lo ife | Wọ́n máa ọmọlanke | 1 |
Yoruba | Lára nǹkan Ọ̀ṣọ́ ni | Páńda náà wà | Wúrà náà wà | 1 |
Yoruba | Kí ni alágbẹ̀dẹ le lò láti rọ ohun èlò onídẹ? | Idẹ ni alágbẹ̀dẹ le lò láti rọ ohun èlò onídẹ | Ẹ̀mú ni alágbẹ̀dẹ le lò láti rọ ohun èlò onídẹ | 0 |
Yoruba | Kí ni ará nǹkan tí alágbẹ̀dẹ fí máa ṣe ohun èlò ọ̀ṣọ́? | Owú ni ara nǹkan tí alágbẹ̀dẹ fí máa ṣe ohun èlò ọ̀ṣọ́ | Òjé ni ara nǹkan tí alágbẹ̀dẹ fí máa ṣe ohun èlò ọ̀ṣọ́ | 1 |
Yoruba | Tí mo bá fẹ́ nǹkan olówó iyebíye yàtọ̀ sí wúrà | Fàdákà ni màá yàn láàyò | Òkúta ni màá yàn láàyò | 0 |
Yoruba | Torí kí ni wọ́n máa ń sun igi ńláǹlà níná | Nítorí èédú ni wọ́n ṣe máa ń sún igi ńláǹlà níná | Nítorí éérú ni wọ́n ṣe máa ń sún igi ńláǹlà níná | 0 |
Yoruba | Kí ni nǹkan mìíràn tí a tún le ri lára epo rọ̀bì? | Epo pupa ni nǹkan mìíràn tí a tún lè rí lára bẹntiró | epo bẹntiró ni nǹkan mìíràn tí a tún lè rí lára bẹntiró | 1 |
Yoruba | Tí mo bá fẹ́ kí ilé mi tuntun rẹwà ní àwọ̀ | Màá lo ọ̀dà tí ó rẹwà | Màá lo ìyèpẹ̀ tí ó rẹ̀wà | 0 |
Yoruba | Lára ibo ni a ti le rí epo òyìnbó | Lára epo rọ̀bì ni a ti le rí epo òyìnbó | Lára ẹyìn ọ̀pẹ́ ni a ti le rí epo òyìnbó | 0 |
Yoruba | Kí tún ni a lè fi ṣe ìkòkò ìdáná lẹ́yìn amọ̀? | Òkúta ni a tún le fi ṣe ìkòkò ìdáná lẹ́yìn amọ̀ | Irin ni a tún le fi ṣe ìkòkò ìdáná lẹ́yìn amọ̀ | 1 |
Yoruba | Tí ó bá fẹ́ sọdá odò sí òdìkejì | Gun orí pákó kọjá | Gun orí àfárá kọjá | 1 |
Yoruba | Kíni màá fi nu omi tí ó dà sílẹ̀ nínú ilé? | Aṣọ inùlẹ̀ tí ó gbẹ́ ní màá lò | Aṣọ ìwọ̀sùn tí ó gbẹ́ ní màá lò | 0 |
Yoruba | Láti mú kí aṣọ fífọ̀ mi yá kíákíá, kí ni mo le lò? | ẹ̀rọ ìfọbọ | ẹ̀rọ ìfọṣọ | 1 |
Yoruba | Kí ni ọ̀kan pàtàkì lára irinṣẹ́ aránṣọ? | Ọmọrogùn jẹ ọ̀kan pàtàkì lára irinṣẹ́ aránṣọ | Abẹ́rẹ́ jẹ́ ọ̀kan pàtàkì lára irinṣẹ́ aránṣọ | 1 |
Yoruba | Kí ni wọ́n fi ń ṣe gààrí? | Gbágùúdá/ẹ̀gẹ́ ni wọ́n fi ń ṣe gààrí | Ọ̀pẹ̀-òyìnbó ni wọ́n fi ń ṣe gààrí | 0 |
Yoruba | Tí apẹja bá fẹ́ mú ẹja lódò, kí ni yóò lò? | Pàkúté ni apẹja yóò lò láti mú ẹja lódò | Àwọ̀n ni apẹja yóò lò láti mú ẹja lódò | 1 |
Subsets and Splits
No community queries yet
The top public SQL queries from the community will appear here once available.