text
stringlengths
29
5.04k
length
int64
loss
float64
src_token_len
int64
0
1.21k
trg_token_len
int64
0
1.21k
total_token_len
int64
2
1.54k
token_ratio
float64
0
84.3
word_ratio
float64
0
54.5
target_lang
stringclasses
9 values
source_lang
stringclasses
12 values
<translate> --- Tite gba àdéhùn ọdún mẹ́rin mìíràn. <eng>: --- Tite gets new 4 year contract
null
null
10
9
21
1.111
0.875
<eng>
<yor>
<translate> Àjọ tó ń mójú tó bọ́ọ̀lù àfẹsẹ̀gbá lórílẹ̀-èdè Brazil (CBF) ń fi àdéhùn ọdún mẹ́rin mìíràn lọ akọ́nimọ̀ọ́gbá àgbà ikọ̀ náà Tite tòhun tẹnu ìjakúrò nínú ife ẹ̀yẹ agbááyé lẹ́ẹ̀marùn-ún ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ láti ìpele kejì sí àṣekágbá. <eng>: Brazil’s Football Federation (CBF) is offering head coach Tite a new four-yea...
null
null
57
33
92
1.727
1.565
<eng>
<yor>
<translate> Gẹ́gẹ́ bí Globo ìtàkùn ilẹ̀ Brazil ṣe sọ, Ìṣọwọ́ṣiṣẹ́ akọ́nimọ̀ọ́gbá àgbà yìí tẹ́ Àjọ CBF lọ́rùn, wọ́n sì ń fi àdéhùn mìíràn lọ̀ ọ́. <eng>: According to the Brazilian website Globo, CBF is satisfied with the head coach’s work and is offering him a new contract.
null
null
39
27
68
1.444
1.091
<eng>
<yor>
<translate> Ẹni ọdún mẹ́tàdínlọ́gọ́ta gba àkóso ikọ̀ Brazil ní inú oṣù kẹfà ọdún 2016, ó si ran ikọ̀ náà lọ́wọ́ láti pegedé sí inú ife ẹ̀yẹ àgbááyé FIFA ọdún 2018 pẹ̀lú ipò kíní láti inú àwọn orílẹ̀-èdè ilẹ̀ Guusu America. <eng>: The 57-year-old took charge of Brazil in June 2016 helping the team qualify for the 2018 ...
null
null
48
31
81
1.548
1.345
<eng>
<yor>
<translate> Lábẹ́ àkóso Tite, ikọ̀ Brazil ti jáwé olúborí ní ìgbà ogún, wọ́n ta ọ̀mì mẹ́rin wọ́n sì pàdánù lẹ́ẹ̀mejì péré, nínú rẹ̀ ni ìpàdánù ọjọ́ ẹtì (Friday) pẹ̀lú ikọ̀ Belgium. <eng>: Under Tite’s management, Brazil have secured 20 victories and four draws losing only two games so far, including Friday’s defeat to...
null
null
47
29
78
1.621
1.304
<eng>
<yor>