audio audioduration (s) 0.06 22.4 | speaker_id stringlengths 5 5 | text stringlengths 8 161 | language stringclasses 1
value | gender stringclasses 2
values | age_range stringclasses 3
values | phase stringclasses 2
values |
|---|---|---|---|---|---|---|
7T1HD | Irinṣẹ́ orin kan ni goge ni àwùjọ hausa. | yoruba | female | 6-17 | phase 1 | |
PH979 | Mo lọ síbi ìgbéyàwó kan nígbà kan rí níbi tí ìyàwó náà ti ní braid kan tí o lẹ́wà. | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
HZM4L | Ẹ kú àsẹ̀yìndè ni àwọn Yòrùbá ń kí àwọn ọmọ òkú tí ó ṣẹ̀ṣẹ̀ kú | yoruba | female | 30-over | phase 2 | |
G2TEL | Ọkọ̀ Òfurufú náà máa gúnlẹ̀ ní ago méjì ọ̀sán. | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
MGWAM | Kulikuli jẹ́ ǹkan ìpanu tí wọ́n ṣe nípa lílo ẹ̀pà, pẹlu orísìírísìí ǹkan | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
POPB8 | Ṣé ọmọ rẹ̀ ọkùnrin wà níbí? | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
WL2XZ | Ìbùdókọ̀ Yaba ni wọ́n ti ń ta pọfupọ́ọ̀fù gbígbóná | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
811Y2 | Irora àyà le ja si iku | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
TQKTS | Kí ọmọdé máa lúwẹ̀ẹ́ lódò léwù púpọ̀ | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
AQBNL | Mo rí igi tí wọ́n fi ń gbẹ́ ère | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
WZQVZ | Ó rí àwọn nkan irin tí ó farasin nínú igi. | yoruba | female | 6-17 | phase 1 | |
GNNQV | Àlọ́ máa ń ní kókó ọ̀rọ̀, àwọn ẹ̀dá ìtàn àti ibùdó itan | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
Z6OOO | Irinṣẹ́ àgbẹ̀ ni katakata. | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
K8OYX | Ó ṣubú sí inú ẹrọ̀fọ̀ nígbà tí ó mú ìgò dunkel marun tán. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
DAZNF | Ìjọba tí fí òfin dé títa ọtí líle. | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
BN1ZC | Ẹyẹ na jẹ kòkòrò | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
IQ4HX | Lọ fọn imú rẹ! | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
JCGP7 | àláǹgbá láyé ìgbàkan ní eran ara dáradára | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
MGWAM | Bẹ́ẹ̀ni, a ti gbégi lé ìgbéyàwó | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
FB2CO | Àwọn òṣìṣẹ́ kọmíṣọ́ọ̀nù máa ń ran èrò lọ́wọ́ láti ra tíkẹ̀ẹ̀tì tàbí láti wá ọkọ̀. | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
II8KP | Ní àkókò yìí ní ọ̀la, Shola yóò máa jẹ ànàmọ́ àti ẹyin dídì. | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
5TLPT | N jẹ ó pín Kùnú náà ni ọ̀la. | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
A53P7 | Mo sọ pé ko ye tẹ rorẹ ojú rẹ! | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
BN1ZC | Ọṣẹ ìwẹ̀ náà wà nínú ikẹ ọṣẹ. | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
AI6WB | Páìpù ààbò ń tọ́jú fún àìlewu | yoruba | male | 6-17 | phase 1 | |
7TZW9 | Omobìnrin ọ̀gbẹ́ni ọlá ti n wúkọ́ láti èkan | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
2SCF8 | Ìforígbárí nínú ìgbéyàwó wọ́pọ̀ lóde òní | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
I9GCJ | Ìjẹta ni egbò ẹsẹ̀ Abíọ́lá jinná. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
A7A2R | Mọ́tò méjì ni bàbá mi ní? | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
5Z6XO | Ọkọ̀ ojú irin tí a bá rìn kò fi bẹ́ẹ̀ wọ̀. | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
KSYPO | Ìyá àgbà ní àdí àgbọn má ń mu ara dán | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
TR90J | Pa òwé nípa ọmọdé fún mi! | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
75CSA | Àwọn oníbàárà lè yàn lára ọ̀pọ̀lọpọ̀ oúnjẹ àti àwọn ohun mímu tó wà ní ìwé àsàyàn náà | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
2URNR | Àwọn ológun o kì í fi bẹ́ẹ̀ rẹ́rìn-ín. | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
SMW9K | Bọ́lá máa kọrin. | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
05T3D | Àbúrò kọ́nẹ́ẹ̀lì ni Àbẹ̀bí | yoruba | female | 6-17 | phase 1 | |
AYARU | Yan àwọn olùdíje fún ìdìbò tó ń bọ̀. | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
BN1ZC | Kí ẹ̀yàn kan sọ fún mi, kíló dé tí ọjà Sítọ́ọ́kì bàjẹ́? | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
64E8A | Bàbá ti pàse pé kí wón yéé dá bàtà òfò sí enu ònà òhun. | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
GDGSD | Àwọn àgbẹ̀ máa ṣiṣẹ́ kára nínú oko | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
AA0QX | Mo fẹ́ ra ẹ̀rọ ìbánisọ̀rọ̀ mìíràn ní ọ̀la | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
RUYB2 | A ti rí ọmokùnrin tí ó jẹ́ Òjó | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
4NKV8 | Ìṣèjọba afẹ̀sìndarí ní nígbà tí òòsà bá n jọba nílu latara olùṣọ. | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
AU54U | Orùká jẹ́ nǹkan pàtàkí tí àọ ènìyàn máa ń fún ara wọn lásìkò ìgbéyàwó láti fi ìfẹ́ hàn. | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
VAO6L | A máa nílò dígà fún iṣẹ́ náà. | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
SV45R | Bẹ́ẹ̀ni, mo wà ní ojúbọ | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
2SCF8 | Ọ̀pọ̀ nǹkan ni wọ́n ń lò nínú ayẹyẹ náà. | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
PCI9Z | Bẹ́ẹ̀ni, mo mọ Ayinla Omowura. | yoruba | female | 6-17 | phase 1 | |
80W5Y | Mi ò rí ara mi gẹ́gẹ́ bí òṣìṣẹ́ báǹkì lọ́dún márùn-ún sí ìsinyìí | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
U5JZU | Àwọn ilé gbówólórí ní àwọn agbègbè ìlú. | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
VAO6L | Tádé ń lọ sí orí òkè | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
VH6DZ | Bímpé àti Adélékè ti fi ìgbéyàwó ọdún mẹ́tàlá sílè lóṣù Belu tó kọjá | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
W8MQ2 | Àwọn obìnrin máa lọ síbi ayẹyẹ náà. | yoruba | female | 30-over | phase 2 | |
I9GCJ | Ó jẹ́ ibi gbígbé oríṣìíríṣìí n kan | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
D7N9Z | Yoruba karamasiki imura torí wọn gbàgbó pé ìrínisí ni ìsọnilọ́jọ̀. | yoruba | female | 6-17 | phase 1 | |
7TZW9 | Ọmọ mí rìn yẹ́nkẹ́n fún ìgbà díẹ̀ kí ó tó bẹ̀rẹ̀ sí ní rìn. | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
IO193 | Àwọn olùkọ́ náà nílò ìdánilẹ́kọ̀ọ́ | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
2DBMP | Tí o bá mu ọtí amuju, wà á má a ta bíọ́bíọ́ | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
Q6KV2 | Òní ni a lọ rí ọmọ náà | yoruba | female | 30-over | phase 2 | |
8LWEK | Bo àkàrà òyìnbó náà | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
KSYPO | Tòmátì ọlọ́ràá máa ń jẹ́ kí oúnjẹ pọ́n | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
WC31P | Ìgbéyàwó máa ń so ẹbí méjì papọ̀. | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
ELC7E | Mo le ṣe Chess | yoruba | male | 30-over | phase 2 | |
OJ8UO | Obìnrin fẹ́ràn oge síṣe púpọ̀. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
XTEFB | Ǹjé̩ o ó jísé̩ mi fún Káyó̩dè ló̩la? | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
BOY4H | Àyè ìjókòó Ọmọlará ti gbáradì fún èrò. | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
SCMQD | Mo máa bá ọ̀kan lára àwọn aṣojú MTN tó máa fèsì sí àwọn oníbàárà dọ́rẹ̀ẹ́ lọ́jọ́ kan | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
F0H5B | Ẹ̀ka ẹ̀kọ́ iṣẹ́ nọ́ọ̀sì wà ní tòsí ilé ìkàwé yunifásítì | yoruba | male | 6-17 | phase 1 | |
W8MQ2 | ilé ìwé náà ń kùnà nínú ojúṣe wọn nínú ẹ̀mí lórí àwọn akẹ́kọ̀ọ́ wọn | yoruba | female | 30-over | phase 2 | |
W8MQ2 | Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ń kọ ìwé wọn. | yoruba | female | 30-over | phase 2 | |
JL658 | Ó ti ṣe ọ́lú baàkì. | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
LA0Y9 | Obìnrin náà gba ọmọ rẹ̀ gbọ́. | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
AVOG6 | Bẹ́ẹ̀ni, mo máa gba aṣọ àǹkóò mi ní ọ̀sẹ̀ tó ń bọ̀. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
QI89N | Bẹ́ẹ̀ni, mo ń tún afaná-ọkọ̀ náà ṣe. | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
GX1SC | ọṣẹ dúdú ni mo fí wẹ̀ | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
KGKZ4 | Àwọn ẹ̀sọ́ aláàbò pápákọ̀ òfurufú máa n yẹ ara ènìyàn wò ki ènìyàn tó wo ọkọ̀ ojú òfurufú | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
MF6K9 | àgbò oògùn ní àwọn ọmọ oògùn wá. | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
OVFI5 | Ó ra àgbàdo sísun dípò èyí tí wọ́n bọ̀ lálẹ́ àná | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
II8KP | Ìjọ Àgùdà jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ìjọ tí ó ti pẹ́ jù ní Nàíjíríà. | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
2SCF8 | Àtẹ̀dúró ọ̀kadà mi ń yọnu. | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
O0GW8 | Mọ̀ n ṣọ fun wọn nípa Madam Koi Koi kí wọn lè tẹtẹ̀ sún làlẹ̀ ọ̀ní. | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
AHN2M | Táyà jẹ́ ara rọ́bà tí ń kan ọ̀nà | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
E2UEX | Òògùn àfẹ́sódì wọ́pọ̀ láàrin ọ́dọ̀ | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
KY5I7 | Ṣé o jẹ ẹ̀wà là na? | yoruba | female | 30-over | phase 2 | |
WPFDW | Ṣe o ni ọgbin iresi? | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
OY31B | Olórí máa ń tọjú àwọn ẹrú náà dáradára. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
MWKK9 | Ade! fí òòrùn gbẹ àwọn èràn nà. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
MGWAM | Tolu hàn lórí ilé isẹ amohun maworan | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
7TZW9 | Ní ayé àtijọ́ awọn bàbá wa gbàgbọ́ pé ọmọ obìnrin kò gbọ́dọ̀ kàwé. | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
BPFNB | Ilé èkò gigá pò ni Nàijiriá | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
KKRSZ | Ìyá mi ma n se ègusi Ìjẹ̀bú tẹ́lẹ̀. | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
OVFI5 | Ǹjẹ́ o tí bá onínàbì ni àjọṣepọ̀ rí? | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
KY5I7 | Mo ti pàrọ̀ ìdèdí | yoruba | female | 30-over | phase 2 | |
HZM4L | Yetunde dára nínú iṣẹ́ ọnà ìbílẹ̀ Yorùbá. Bimpe ń ṣiṣẹ́ ní ìtọ́jú ìlera. | yoruba | female | 30-over | phase 2 | |
V8VTJ | Má wá ní àsìkò ọdún Orò. | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
XBPXV | Ní áyé àtijọ́, àmútọ̀run wá ní irun dada jẹ́. | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
U600K | Ṣọlá se oúnjẹ yẹn! | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
TKWIS | Ọpẹ́yẹmí jẹ́ onígbọràn ọmọ | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
SDJ13 | Wọn mú Kọlá nítorí pé ó jí òwò lọwọ́ ọ̀gá rẹ. | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
YT0T2 | Àbúrò bàbá mi ni Badmus. | yoruba | male | 18-29 | phase 2 |
End of preview. Expand in Data Studio
README.md exists but content is empty.
- Downloads last month
- 22