Dataset Viewer
Auto-converted to Parquet Duplicate
audio
audioduration (s)
0.06
18.9
speaker_id
stringlengths
5
5
text
stringlengths
7
193
language
stringclasses
1 value
gender
stringclasses
2 values
age_range
stringclasses
3 values
phase
stringclasses
2 values
T0W7N
Ṣe awọn oṣiṣẹ iṣoogun yoo wa lori ọkọ?
yoruba
female
30-over
phase 1
NSVL6
Dide kí ọrẹ rẹ
yoruba
female
6-17
phase 1
DVEZH
Ile-iṣọ iṣakoso yarayara dahun lati jẹrisi nọmba ọkọ ofurufu ati pese idasilẹ si ilẹ
yoruba
male
30-over
phase 1
ZB24U
Wara ti nutri náà jábọ́ lọ́wọ Fúnmbí.
yoruba
male
6-17
phase 1
VUGDK
Màá gba Ìmọ̀ràn olùdarí ilé-ìfowópamọ́sí náà.
yoruba
female
30-over
phase 1
LCOS2
Ìgbàwo ni wọ́n se moinmoin?
yoruba
male
18-29
phase 1
DMYGK
Ẹbí Bọ̀dé máa ń bọ Òrìṣà Ògún láti le ní àlùyọ nínú iṣẹ́ ọdẹ ṣíṣe wọn.
yoruba
female
18-29
phase 1
VAO6L
Ibori ti iyawo mi lo fun igbeyawo wa jẹ gbowolori
yoruba
male
18-29
phase 2
S9PH2
Àwọn abúlé ìfẹ̀yìntì lẹ́nu iṣẹ́ ń ṣe ìtọ́jú àwọn àgbàlagbà
yoruba
female
18-29
phase 1
2JZTK
Nìbó ni èwúrò ná wà
yoruba
female
18-29
phase 1
VH6DZ
Iṣẹ́ ipeja ni Bimbo ń ṣe.
yoruba
male
18-29
phase 1
HJ0C8
Aláńgbàá máa ń fi ikùn rìn.
yoruba
male
18-29
phase 1
59INZ
Diẹ ninu awọn oriṣi ope oyinbo le fa rilara sisun ni ẹnu rẹ nigbati o jẹun
yoruba
male
18-29
phase 2
W8MQ2
olùkó kò wá nípa Ọlọba aládé
yoruba
female
30-over
phase 2
VKW4W
Ọdún tí ó lọ ni a bẹ̀rẹ̀ sí í ní lo gáàsì.
yoruba
male
18-29
phase 1
QWZAL
Mo lọ sí ààfin ní oṣu tí ó kọjá.
yoruba
male
30-over
phase 1
2SCF8
Ìyá mi ko tun lè jí wá sí ayé nitori wọn ti kú.
yoruba
female
18-29
phase 2
Q6KV2
Ǹjẹ́ eré àgbéléwò tàtọ̀húnrìnwá kọ́ ló mú àṣàkaṣà wálẹ̀ wa?
yoruba
female
30-over
phase 2
59INZ
Ẹ́tàdínláàdọ̀fà ló tẹ́lẹ̀ Ẹ́rìndínláàdọ́fà
yoruba
male
18-29
phase 2
KY5I7
Ní ọjọ́ iwájú, ìwé tí a lè fọwọ́ kàn kí yóò di rírí ní kíákíá
yoruba
female
30-over
phase 2
AA0QX
Géètì dára tí a bá ní i
yoruba
male
30-over
phase 1
ZHR4X
Mo ma ra sùpàgẹ́tì láti ọ̀dọ̀ Kóredé tí mo bá lọ sí ifásitì Èkó
yoruba
female
18-29
phase 2
OVFI5
Ikú oró ní ó kú
yoruba
female
18-29
phase 2
6GBMY
Níbo ni mà á wà ní ọ̀la nípa ayẹyẹ ìbúra náà?
yoruba
female
18-29
phase 1
0UGA7
Káfíńńtà tí ń lọ.
yoruba
female
18-29
phase 1
KOTV1
aṣọ ìwé ní wón fí nu ará
yoruba
female
18-29
phase 1
F9A7W
wón fí ọti òyìnbó bo òrìsà.
yoruba
male
6-17
phase 1
SRYA7
Gbogbo ènìyàn ni ó yẹ fún láti ní kíńdínrìn méjì.
yoruba
female
18-29
phase 2
JDIDU
Ṣẹ́ iwọ yóò tó ibi-ipa-aṣọ-mọ-sí ní ọ̀lá?
yoruba
female
18-29
phase 1
I4J23
Àwọn ilé mẹ́fà ló wà ní ilé ẹ̀kọ́ náà.
yoruba
female
18-29
phase 1
PA33O
Yóò dí adarí ifásitì tuntun
yoruba
male
18-29
phase 1
W8MQ2
ilé ìwé náà nílò àwọn olùkọ́ sí i
yoruba
female
30-over
phase 2
DBM3L
Ǹjẹ́ kì ń ṣe wípé ìlú Sáúdí jẹ́ ìlú afẹ́síndarí?
yoruba
female
18-29
phase 1
Q7FW1
Ìgò Smirnoff mélòó lo lè mu?
yoruba
female
18-29
phase 2
2T441
Emi yoo kopa ninu Olimpiiki ti nbọ
yoruba
male
18-29
phase 1
F7KH2
Mo máa tijú ìyá àgbà nílé
yoruba
male
18-29
phase 1
XJOPN
Mo fẹ́ tún iná okada mi ṣe.
yoruba
male
30-over
phase 1
YVQQZ
Yin ìbọn náà!, corporal kigbe.
yoruba
female
30-over
phase 1
HPTGN
Kílípù ni a fi ń de wáyà mọ́ ara ògiri
yoruba
female
18-29
phase 2
KSYPO
Tí a bá gbin igi sí àyíká ilé, ó má ń dáàbò bo ilé
yoruba
female
18-29
phase 2
MF6K9
Jígí mọ́tò ní awakọ̀ máa ń fi rí ohun tó ń ṣẹlẹ̀ níta àti ní àyíká mọ́tò rẹ̀.
yoruba
female
30-over
phase 1
V6MKF
Kò sí níbẹ̀ láti súre fún oúnjẹ náà
yoruba
female
18-29
phase 2
7020G
Ọkọ̀ ojú omi tóbi gan-an
yoruba
female
18-29
phase 1
1MMFA
Ǹjẹ́ o ní ìmọ̀ kankan ní pa ìlànà ìbálòpọ̀ àwọn ìkookò?
yoruba
female
6-17
phase 1
VU0FE
Mo máa tọ́jú àwọn àlejò
yoruba
female
30-over
phase 1
CGXXR
Òun ni ó ṣe àtúntò fíìmù onífẹ̀ẹ́ náà.
yoruba
male
18-29
phase 1
HVEP1
Iná eyín món jé pupa nìgbà mí
yoruba
female
30-over
phase 1
MAZXB
Mo ra táwẹ̀lì tuntun
yoruba
male
30-over
phase 1
1GI4G
Obìnrin kò gbọdọ̀ fojú kan orò!
yoruba
female
18-29
phase 1
43FB0
Ta ni ó ń lu ìlù?
yoruba
female
30-over
phase 2
7TZW9
Ǹjẹ́ yàhú yàhú jẹ́ ìwà aburú àwùjọ?
yoruba
male
18-29
phase 2
WZQVZ
Óbìrín mà n ni óyùn fún óṣú mèsãn
yoruba
female
6-17
phase 1
KDXVX
Bẹ́ẹ̀ni, ọkùnrin náà á fẹ́ mi
yoruba
male
18-29
phase 1
W8MQ2
Ẹ̀ṣọ́ ààbò ń dáàbò bo àwọn akẹ́kọ̀ọ́
yoruba
female
30-over
phase 2
9LH7J
Oruko awon oloogun ni Ebuka
yoruba
female
18-29
phase 1
CZ18P
N ò mọ̀ pé eré apanilẹ́rìn-ín ni eré yìí nígbà tí mo rí ìpolówó rẹ̀
yoruba
male
18-29
phase 1
GBD1E
Yàrá ìkàwé ni wọ́n ti máa ń kọ àwọn akẹ́kọ̀ọ́ lẹ́kọ̀ọ́.
yoruba
female
30-over
phase 1
ZLOOP
Ṣé ilé ẹ̀kọ́ gíga ẹ máa ń gba owó ìgbaniwọlé ?
yoruba
male
18-29
phase 2
7T1HD
Àwọn òrìṣà máa ń ní ojúbọ tí a ti ń bọ̀ wọ́n.
yoruba
female
6-17
phase 1
2OZP5
Emi yoo ran ọ lọwọ lati ṣeto ipolongo rẹ
yoruba
female
18-29
phase 1
MGWAM
Ilé-iṣẹ́ ìròyìn ti fi ìròyìn le léde
yoruba
female
18-29
phase 2
Q6KV2
A dúró ni ilé oúnje láti jeun ni alé
yoruba
female
30-over
phase 2
TT9P1
Àjọkẹ́ bí ìbejì ní ọjọ́ àìkú
yoruba
male
30-over
phase 1
1MMFA
Ṣé o ní ṣíṣù?
yoruba
female
6-17
phase 1
0UVE1
Bàbá àgbà ti ra bọ́ọ̀lù fún àwọn ọmọ ọmọ rẹ̀
yoruba
male
18-29
phase 1
EN10J
Igba ooru to kọja, a ṣafikun awọn irọri jiju tuntun lati sọ iwo yara gbigbe naa sọtun.
yoruba
female
18-29
phase 1
UKVCY
Ìyàwó yóò rà yẹtí fún àwọn ọ̀rẹ́ ìyàwó ní ìsọ̀ tí wón ti ń tà á.
yoruba
male
18-29
phase 1
8139X
Awọn àpànirùn iná tó fi sọ̀rọ̀ èró̀ fún pàjàwìrí àti àìlẹ̀wù ni awọn ọfíìsì Nàìjíríà.
yoruba
female
18-29
phase 1
64SJY
Agbẹ̀jọ́ro kékeré náà ṣẹṣẹ jáde nílé ẹ̀kọ́ ofin.
yoruba
male
18-29
phase 1
OVFI5
Sọ ti kúrò ní ọ́fíìsì olórí ẹ̀ká-ẹ̀kọ́?
yoruba
female
18-29
phase 2
FRDIB
GRA (Agbègbè Ìgbé Ìjọba) ṣe àmì ìgbé ayé tí wọ́n ṣètò.
yoruba
male
18-29
phase 1
K6BEN
Bàbá mi kò tí ì dáríjì mí fún irun tí mo gẹ̀ lọ́dún tó kọjá.
yoruba
male
6-17
phase 1
H68JS
Àwọn orin ìgbaanì máa ń ṣàfihàn ìtàn, ìgbàgbọ́ àti ìrírí àwùjọ kan.
yoruba
male
6-17
phase 1
MXTT9
Àwọn aláró ló máa ń ṣe àdìrẹ wa.
yoruba
male
30-over
phase 2
4XT0F
Ó sọ fún mi bí ẹyẹ ṣe yàgbẹ́ sóri àga
yoruba
female
18-29
phase 2
HH0CR
Àwọn yàrá isé maá mú kí isé ó lọ dáradára ní ilé isé
yoruba
male
18-29
phase 2
OYG89
O yẹ kí o kọ́kọ́ gbé kétù léná kí o to gbe apẹ kaná.
yoruba
male
18-29
phase 1
O4Q43
Mo gba ìwé pélébé ní ilé ìfowópamọ́ mi
yoruba
female
30-over
phase 1
ZHR4X
Mo rí bàbá tó ń fi àwọn irinṣẹ́ wọn sí inú ìkóhun-èlò-sí lálẹ́.
yoruba
female
18-29
phase 2
LRMKP
Bàbá ni arí bí olórí fún ìdílé náà.
yoruba
male
30-over
phase 1
TLXES
Wọ́n sọ fún mi pé èdè Yorùbá gbajúmọ̀ ní Nàìjíríà
yoruba
male
30-over
phase 1
FTZ03
Oládùnní máa n ra okòólélé̩́gbè̩fà kátó̩ò̩nù sìgá lós̩oos̩ù
yoruba
female
18-29
phase 1
BN1ZC
Àwọn ọmọ ìyá le máa jowú ara wọn
yoruba
female
18-29
phase 2
V8VTJ
Ṣé o lọ sí ilé ọtí lánàá?
yoruba
female
30-over
phase 1
ECGRM
Báwo ni eégún náà ṣe máa ríran..
yoruba
female
18-29
phase 1
W8MQ2
Àwọn ará ìlú máa wà ní ipò ìdùnnú níbi ìfijoyè ọba tuntun ní ọ̀sẹ̀ tí ó ń bọ̀
yoruba
female
30-over
phase 2
SGO1V
Onímọ̀-ẹ̀rọ ọkọ̀ ofurufú ṣàyẹ̀wò ẹ́ńgíìnì kó tó gbéra.
yoruba
male
18-29
phase 1
G3QJO
Bẹẹni aṣọ gígùn ni a nlo ni ile-ẹkọ Sẹkọndiri wa
yoruba
male
6-17
phase 1
DULER
Garawa náà ti fọ́.
yoruba
female
30-over
phase 1
VLZWS
Wọ́n wọn ẹrù mi
yoruba
female
18-29
phase 1
4XT0F
Àgbon ni ìyá Tóbi máa ń tà
yoruba
female
18-29
phase 2
OJT9K
Rárá, kò le sọ híńdì
yoruba
female
18-29
phase 1
B1H3H
Ọ̀rẹ́ ẹ̀ kòríkòsùn ni Bímpé àti Tọ́lání
yoruba
male
30-over
phase 1
2DBMP
Àwọn ọ̀rẹ́ ló dá ẹ̀mí Mohbad légbodò
yoruba
female
30-over
phase 1
MCVV4
Moti ra ọjà ni Gbọ̀ngán ìtajà náà ri
yoruba
female
30-over
phase 1
W8MQ2
Wón dá ẹjọ́ fún apànìyàn naa
yoruba
female
30-over
phase 2
LA0Y9
A máa yí ẹran àti ẹja náà láta.
yoruba
female
18-29
phase 2
ELC7E
Toba rá Kàmèrá tútún nijètá
yoruba
male
30-over
phase 2
7TZW9
Àwọn ìròyìn àdúgbò sọ̀rọ̀ nípa àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ láwùjọ
yoruba
male
18-29
phase 2
O0GW8
Mọ n rẹti láti jẹ gbogbo ohun tí èmi kò le jẹ lẹ́ẹ̀hin ti mọ bá bí mọ̀.
yoruba
male
18-29
phase 2
End of preview. Expand in Data Studio
README.md exists but content is empty.
Downloads last month
17