Dataset Viewer
Auto-converted to Parquet Duplicate
audio
audioduration (s)
0.06
25.8
speaker_id
stringlengths
5
5
text
stringlengths
4
183
language
stringclasses
1 value
gender
stringclasses
2 values
age_range
stringclasses
3 values
phase
stringclasses
2 values
ELC7E
Àwọn arọ nílò àmújútó dáadáa.
yoruba
male
30-over
phase 2
JNHHS
Ǹjẹ́ a máa rí àdá gé koríko fàfà náà?
yoruba
female
18-29
phase 1
C55LG
Àwọn agbébọn kọlu àwọn arìnrìn-àjò lójú pópó.
yoruba
female
6-17
phase 1
Q54MY
Inú mi máa dùn láti lọ sí ibi tí omi ti ń dà ní Òwú.
yoruba
female
18-29
phase 2
Q54MY
ṣé òwe ni ó dé sí ilé Yorùbá?
yoruba
female
18-29
phase 2
S0O2H
Kò yẹ kí́ o lò búrọ́ọlṣì ìfọyín kan ju oṣù mẹ́ta lọ.
yoruba
male
30-over
phase 1
SRYA7
Ọkọ òfúrufú máa ń lo kerosini gẹ́gẹ́bí epo
yoruba
female
18-29
phase 2
GSS7E
Rara kii ṣe ọkunrin ti o ni iyawo.
yoruba
female
18-29
phase 1
LA0Y9
Ọjọ́ mẹ́ta ni olóyún náà fi ń rọbí kó tó bímọ.
yoruba
female
18-29
phase 2
7O7OY
Ó kú epo karosíìnì kan.
yoruba
female
18-29
phase 1
F6X09
Ìkànṣọ́ ni ojú méjì.
yoruba
male
6-17
phase 1
64E8A
Fẹ́mi yá owó lọ́wọ́ ilé ẹ̀dínwó.
yoruba
male
18-29
phase 1
ZHR4X
Mo máa ń lọ ibùdó omi ní èèkàn ní oṣù.
yoruba
female
18-29
phase 2
43FB0
Bẹ́ẹ̀ni, mo máa ń gbé aṣọ mi lọ sí yàrá-ìfọṣọ ní ilé-ìtura náà.
yoruba
female
30-over
phase 2
LET8H
Mò ń jẹ ṣíkìnnì àti ṣiipusi pẹ̀lú kẹ́ṣọpù
yoruba
male
18-29
phase 1
QZGFT
Ẹ̀wà àti búrẹ́dì jẹ́ àjẹpọ̀ óúnjẹ tí ó gbajúmọ̀ jù
yoruba
female
30-over
phase 1
ELC7E
Ilé-Iwósán ni Kola wá làná
yoruba
male
30-over
phase 2
OZCG2
Lámilámi le pín àìsàn.
yoruba
female
30-over
phase 2
Q6KV2
Ogún ọmọdé kò lè ṣeré fún ogún ọdún.
yoruba
female
30-over
phase 2
OVFI5
Fún ọmọ náà ní igo oúnjẹ rẹ! ìyá rẹ pàṣẹ
yoruba
female
18-29
phase 2
4BH1U
A o ṣè apádẹ̀ kán ní ọ̀fíìsì olórí ilẹ̀-iwé na.
yoruba
male
18-29
phase 1
JKM73
Kínní o ṣẹlẹ sí ìyá arúgbó náà?
yoruba
male
18-29
phase 1
0205X
Oríṣiríṣi igi ló wà.
yoruba
female
18-29
phase 1
JKXVQ
Ìyá ọlọ́jà náà yóò tọ́jú owó-ẹyọ rẹ̀.
yoruba
female
18-29
phase 1
QV6RB
Jígà tuntun ni bíríkìlà náà kó wá
yoruba
male
18-29
phase 1
LOISH
Ọdẹ náà pa ẹfọ̀n.
yoruba
female
18-29
phase 1
O6U9S
Àfẹ́sọ́nà ni orúkọ fún ọkùnrin tí ó ti fẹ́ láya
yoruba
female
18-29
phase 1
59INZ
O tí gbe ìwé tó kọ sóri Researchgate láti ọjó yí
yoruba
male
18-29
phase 2
DK6N8
Ìbàdàn ni màá wà ní Kérésìmesì tí ó ń bọ̀
yoruba
female
18-29
phase 1
3D9SN
Ni igba atijọ, awọn ohun elo ibi idana bi awọn odo jẹ pataki fun lilọ pẹlu ọwọ ati awọn eroja lilu
yoruba
female
30-over
phase 1
HL8TT
Àlọ́ àpamọ̀ ni mo ń kọ́ àwọn akẹ́kọ̀ọ́.
yoruba
female
30-over
phase 1
V3PYU
Ìyá àgbà sọ fún mi pé tí mo bá sín gbẹ́rẹ́ màá lágbára.
yoruba
male
30-over
phase 1
NOSZI
Àwọn kòkòrò kan wà tí ó jẹ́ pé inú igbó ni wọ́n sábà má ń wà
yoruba
female
30-over
phase 1
8FVN5
Yẹkìnì dé alangba mó inú àgọlọ.
yoruba
female
18-29
phase 1
HH0CR
Ọ́fíìsì akọ̀wé wa wà ní iwájú ọ́fíìsì adarí ẹ̀kọ́ náà.
yoruba
male
18-29
phase 2
HPTGN
Awọn oniwosan elegbogi yoo gba imọ-ẹrọ tuntun lati mu iṣakoso oogun ṣiṣẹ
yoruba
female
18-29
phase 2
0PXRU
Radiétọ̀ ọkọ̀ náà kò ṣiṣẹ́ mọ́
yoruba
male
18-29
phase 1
G15QO
Olu ló fún mi ní igba náírà
yoruba
male
18-29
phase 1
MGWAM
Àwọn amòfin náà wà ní ilé ejọ́
yoruba
female
18-29
phase 2
2VGOD
Alágbẹ̀dẹ ń rọ ọkọ́ tuntun
yoruba
female
18-29
phase 1
2SCF8
Ìyá àgbà mi ni ó ṣe irú àbúrò mi
yoruba
female
18-29
phase 2
BN1ZC
Ẹ̀ka tí ó ń kọ́ nípa ìtàn n i à ń pè ní ẹka ìmọ̀ ìtàn
yoruba
female
18-29
phase 2
2EBXD
Àwọn ọmọdé máa ń ṣeré ní Ibùdó-ìgbafẹ́.
yoruba
female
30-over
phase 1
43FB0
Bẹ́ẹ̀ni, oníròyìn ni Bọ́lá.
yoruba
female
30-over
phase 2
HH0CR
Ọba ìlú wa lo ìlèkè funfun
yoruba
male
18-29
phase 2
K12YZ
Wọ́n wọ ọkọ̀-òfurufú lọ sí Àbújá lánàá.
yoruba
male
18-29
phase 1
A9UWZ
Bá mi lọ ra ọsàn méjì wá
yoruba
male
30-over
phase 1
MGWAM
Orí kan ni mo ní
yoruba
female
18-29
phase 2
GLELE
Labalábá yóò di kòkòrò pàtàkì
yoruba
male
18-29
phase 1
LFWC9
O gbọdọ̀ mú káádì ìdánimọ̀ rẹ wa sí ọ́físì adarí ẹ̀ka ẹ̀kọ́ lọ́la.
yoruba
male
30-over
phase 1
PKHBQ
Àwọn ọmọ-ẹgbẹ́ ẹgúngún máa ṣe ọdún egúngún ní ọ̀la.
yoruba
male
30-over
phase 1
59INZ
Ṣé ṣáìnì náà já lánàá?
yoruba
male
18-29
phase 2
2PIY6
Aṣọ ìdọ̀tí kún orí ibùsùn náà.
yoruba
male
18-29
phase 1
SEVGS
Ilé ìtura ayé òde òní máa sì ni àwọn ilẹkun ẹ̀rọ ayélujára.
yoruba
male
30-over
phase 1
DN5E8
Bẹ̀ẹ́ni, má a ṣe ìgbéyàwó musulumi.
yoruba
male
30-over
phase 1
F0U8E
Mà á lo fìtílà àgbésórí tábìlì láti kàwé.
yoruba
female
30-over
phase 1
ERQYO
Ṣé o fẹ́ràn láti máa ṣe knotless braid?
yoruba
female
30-over
phase 1
VAO6L
Yàrá ìbùsùn ni ibi tí a máa ń gbé ìbùsùn sí tí a sì máa ń sún
yoruba
male
18-29
phase 2
II1GD
Ní ìgbà tí ebi bá ń pa àwọn ọmọdé, wón á bú sí igbe.
yoruba
male
30-over
phase 1
GTI5O
Ìgbẹ́kẹ̀lé jẹ́ ìpìlẹ̀ ìbáṣepọ̀ ìlera àti ìbáṣepọ̀.
yoruba
male
18-29
phase 1
HZM4L
Ó kọrin ní ṣọ́ọ̀ṣì lọ́la!
yoruba
female
30-over
phase 2
4NQNM
Ìlèkùn onigi ti kán.
yoruba
male
30-over
phase 1
Q7FW1
Mo ní òògùn ibà oníkóró méjì péré ni kí o lò lánàá
yoruba
female
18-29
phase 2
Q54MY
Idris ni àwòrán àádọta.
yoruba
female
18-29
phase 2
Q6KV2
Awọn oluyọọda ati awọn alabojuto ikẹkọ ni idagbasoke ọmọde wa ni awọn ile awọn ọmọ ti ko ni iya
yoruba
female
30-over
phase 2
4XT0F
Yóò tó ma ṣiṣẹ́ ní ṣíṣe ni èbúté ọkọ̀ ojú omi
yoruba
female
18-29
phase 2
4MJ2L
Ṣe o mọ̀ itàn Àmìnà jagunjagun naà?
yoruba
male
18-29
phase 1
JKNY4
Adebisi ni ó tà kúlíkúlí náà fún mi.
yoruba
female
18-29
phase 1
82HCV
Iṣu ègé mẹ́ta ni mò ń jẹ.
yoruba
female
30-over
phase 1
MZLHM
Bọ̀wọ̀ fún Danfari! Ọkùnrin náà wí.
yoruba
male
18-29
phase 2
2SCF8
Ìyá mi yóò lọ Guaranty Trust Báńkì lọ́la.
yoruba
female
18-29
phase 2
LA0Y9
Malamu náà ta òrùka ìgbéyàwó olówó iyebíye.
yoruba
female
18-29
phase 2
BNQBX
Ṣé o lọ fún iṣẹ́ àṣewò nínú yàrá àyẹ̀wò físììsì?
yoruba
female
18-29
phase 1
J8C9N
Ó pàdé Esther ní ilè ìjósìn.
yoruba
female
18-29
phase 1
43FB0
Bẹ́ẹ̀ni, mo dábẹ́ fún ọmọkùnrin náà lásìkò
yoruba
female
30-over
phase 2
C2C69
Tọ́jú ilé àwọn ọmọ aláìlóbi!
yoruba
female
30-over
phase 1
E9NLH
Mo ti darapọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ àwọn oníròyìn ilé ìwé tí ifáfitì Ilorin.
yoruba
female
18-29
phase 1
K7EWM
Adé yóò bá wọn sọ̀rọ̀ lọ́nà tí kò gbẹ̀fẹ̀!
yoruba
female
30-over
phase 1
CB5AR
àwọn àgùtàn jẹ́ onísùúrù
yoruba
male
18-29
phase 1
O0GW8
Ṣẹ̀ o tẹlẹ̀ mi lórí Twitter?
yoruba
male
18-29
phase 2
FPAKJ
Ẹranko ẹlẹ́sẹ̀ mẹ́rin tó tóbi ni màlúù.
yoruba
female
18-29
phase 1
43FB0
Kí ló dé tí ò ń fò?
yoruba
female
30-over
phase 2
M9HCB
O gbọ́dọ̀ wà ojútùú àdáyébá sí ìṣòro náà
yoruba
female
18-29
phase 1
4BH1U
Ìlẹ̀kùn tí wọ́n lò yẹn la ma ma lò
yoruba
male
18-29
phase 1
Q7FW1
Orí mi ṣí láàárọ̀ fúnṣẹ́ nínú ọkọ̀ àmọ́ mi ò lè ṣíṣe nítorí ẹjọ́ tọ́lọ́kọ̀ bá mi rò.
yoruba
female
18-29
phase 2
6RQ4Y
Jídé ń ta irinṣẹ́ kápẹ́ntà àti ti ìkọ́lé ní ọjà Ìsìnkàn
yoruba
male
30-over
phase 1
ZU5PK
Gbé Kọ̀mpútà alágbèéká tí o gbé lọ wá
yoruba
male
18-29
phase 1
HZM4L
Ìgbàgbọ́ ni wípé àwọn sista ṣìní ìbàlé wọn
yoruba
female
30-over
phase 2
JKPBW
Ó paálásẹ pé kí ó má fí àtìlẹ́yìn hàn fún ìjọba ológun níbi ìdíje ilé ìwé rẹ̀
yoruba
female
18-29
phase 1
GFQXI
Ọ̀la ni òrò ìyàwó tuntun.
yoruba
female
18-29
phase 1
V6MKF
Iyá mi rá ọ̀pọ̀lọ́pọ̀ awọn núdúlù ìfé́ fún mí nígbàtí ó ṣàbẹ̀wò sí New York ní òdún tó kọja.
yoruba
female
18-29
phase 2
8DNTD
Ṣolá ní bàbá òun ṣe ètùtù airomobi fún òun àti ìyàwó rẹ.
yoruba
male
18-29
phase 1
DMM7Q
Mo fẹ́ bo ọ̀gẹ̀dẹ̀ dúdú tí wọ́n fún mi títí tí yóò fi pọ́n.
yoruba
male
30-over
phase 1
OYBT6
O gbọ́dọ̀ ní onídúró kí o yá owó
yoruba
male
18-29
phase 1
BOH7B
Yóò ra ìṣó tí ó dára
yoruba
male
18-29
phase 1
CMYT1
Ìpele ìbàraeni sòrò láàrin olùkó àti akékòó
yoruba
male
18-29
phase 1
P73VN
Lọ pé olórí ẹ̀ka ẹ̀kọ́ èdè Gẹ̀ẹ́sì fún mi!
yoruba
female
30-over
phase 1
XTEFB
Ni diẹ ninu awọn aṣa, obinrin wẹ pẹlu omi oku.
yoruba
female
18-29
phase 1
LR4Z9
Ẹ̀ka ogun ilẹ̀ Nàìjíríà ní ẹ̀ka mẹ́ta; Ámì Nàìjíríà, ẹ̀ka ogun orí-omi Nàìjíríà àti ẹ̀ka ogun ojú-òfurufú Nàìjíríà.
yoruba
female
30-over
phase 1
LGUC3
Adesewa má dàgbà láti dì gbajúmò Olorin
yoruba
female
18-29
phase 1
End of preview. Expand in Data Studio
README.md exists but content is empty.
Downloads last month
1