audio audioduration (s) 0.06 25.8 | speaker_id stringlengths 5 5 | text stringlengths 4 183 | language stringclasses 1
value | gender stringclasses 2
values | age_range stringclasses 3
values | phase stringclasses 2
values |
|---|---|---|---|---|---|---|
ELC7E | Àwọn arọ nílò àmújútó dáadáa. | yoruba | male | 30-over | phase 2 | |
JNHHS | Ǹjẹ́ a máa rí àdá gé koríko fàfà náà? | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
C55LG | Àwọn agbébọn kọlu àwọn arìnrìn-àjò lójú pópó. | yoruba | female | 6-17 | phase 1 | |
Q54MY | Inú mi máa dùn láti lọ sí ibi tí omi ti ń dà ní Òwú. | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
Q54MY | ṣé òwe ni ó dé sí ilé Yorùbá? | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
S0O2H | Kò yẹ kí́ o lò búrọ́ọlṣì ìfọyín kan ju oṣù mẹ́ta lọ. | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
SRYA7 | Ọkọ òfúrufú máa ń lo kerosini gẹ́gẹ́bí epo | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
GSS7E | Rara kii ṣe ọkunrin ti o ni iyawo. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
LA0Y9 | Ọjọ́ mẹ́ta ni olóyún náà fi ń rọbí kó tó bímọ. | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
7O7OY | Ó kú epo karosíìnì kan. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
F6X09 | Ìkànṣọ́ ni ojú méjì. | yoruba | male | 6-17 | phase 1 | |
64E8A | Fẹ́mi yá owó lọ́wọ́ ilé ẹ̀dínwó. | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
ZHR4X | Mo máa ń lọ ibùdó omi ní èèkàn ní oṣù. | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
43FB0 | Bẹ́ẹ̀ni, mo máa ń gbé aṣọ mi lọ sí yàrá-ìfọṣọ ní ilé-ìtura náà. | yoruba | female | 30-over | phase 2 | |
LET8H | Mò ń jẹ ṣíkìnnì àti ṣiipusi pẹ̀lú kẹ́ṣọpù | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
QZGFT | Ẹ̀wà àti búrẹ́dì jẹ́ àjẹpọ̀ óúnjẹ tí ó gbajúmọ̀ jù | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
ELC7E | Ilé-Iwósán ni Kola wá làná | yoruba | male | 30-over | phase 2 | |
OZCG2 | Lámilámi le pín àìsàn. | yoruba | female | 30-over | phase 2 | |
Q6KV2 | Ogún ọmọdé kò lè ṣeré fún ogún ọdún. | yoruba | female | 30-over | phase 2 | |
OVFI5 | Fún ọmọ náà ní igo oúnjẹ rẹ! ìyá rẹ pàṣẹ | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
4BH1U | A o ṣè apádẹ̀ kán ní ọ̀fíìsì olórí ilẹ̀-iwé na. | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
JKM73 | Kínní o ṣẹlẹ sí ìyá arúgbó náà? | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
0205X | Oríṣiríṣi igi ló wà. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
JKXVQ | Ìyá ọlọ́jà náà yóò tọ́jú owó-ẹyọ rẹ̀. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
QV6RB | Jígà tuntun ni bíríkìlà náà kó wá | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
LOISH | Ọdẹ náà pa ẹfọ̀n. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
O6U9S | Àfẹ́sọ́nà ni orúkọ fún ọkùnrin tí ó ti fẹ́ láya | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
59INZ | O tí gbe ìwé tó kọ sóri Researchgate láti ọjó yí | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
DK6N8 | Ìbàdàn ni màá wà ní Kérésìmesì tí ó ń bọ̀ | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
3D9SN | Ni igba atijọ, awọn ohun elo ibi idana bi awọn odo jẹ pataki fun lilọ pẹlu ọwọ ati awọn eroja lilu | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
HL8TT | Àlọ́ àpamọ̀ ni mo ń kọ́ àwọn akẹ́kọ̀ọ́. | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
V3PYU | Ìyá àgbà sọ fún mi pé tí mo bá sín gbẹ́rẹ́ màá lágbára. | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
NOSZI | Àwọn kòkòrò kan wà tí ó jẹ́ pé inú igbó ni wọ́n sábà má ń wà | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
8FVN5 | Yẹkìnì dé alangba mó inú àgọlọ. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
HH0CR | Ọ́fíìsì akọ̀wé wa wà ní iwájú ọ́fíìsì adarí ẹ̀kọ́ náà. | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
HPTGN | Awọn oniwosan elegbogi yoo gba imọ-ẹrọ tuntun lati mu iṣakoso oogun ṣiṣẹ | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
0PXRU | Radiétọ̀ ọkọ̀ náà kò ṣiṣẹ́ mọ́ | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
G15QO | Olu ló fún mi ní igba náírà | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
MGWAM | Àwọn amòfin náà wà ní ilé ejọ́ | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
2VGOD | Alágbẹ̀dẹ ń rọ ọkọ́ tuntun | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
2SCF8 | Ìyá àgbà mi ni ó ṣe irú àbúrò mi | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
BN1ZC | Ẹ̀ka tí ó ń kọ́ nípa ìtàn n i à ń pè ní ẹka ìmọ̀ ìtàn | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
2EBXD | Àwọn ọmọdé máa ń ṣeré ní Ibùdó-ìgbafẹ́. | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
43FB0 | Bẹ́ẹ̀ni, oníròyìn ni Bọ́lá. | yoruba | female | 30-over | phase 2 | |
HH0CR | Ọba ìlú wa lo ìlèkè funfun | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
K12YZ | Wọ́n wọ ọkọ̀-òfurufú lọ sí Àbújá lánàá. | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
A9UWZ | Bá mi lọ ra ọsàn méjì wá | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
MGWAM | Orí kan ni mo ní | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
GLELE | Labalábá yóò di kòkòrò pàtàkì | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
LFWC9 | O gbọdọ̀ mú káádì ìdánimọ̀ rẹ wa sí ọ́físì adarí ẹ̀ka ẹ̀kọ́ lọ́la. | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
PKHBQ | Àwọn ọmọ-ẹgbẹ́ ẹgúngún máa ṣe ọdún egúngún ní ọ̀la. | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
59INZ | Ṣé ṣáìnì náà já lánàá? | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
2PIY6 | Aṣọ ìdọ̀tí kún orí ibùsùn náà. | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
SEVGS | Ilé ìtura ayé òde òní máa sì ni àwọn ilẹkun ẹ̀rọ ayélujára. | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
DN5E8 | Bẹ̀ẹ́ni, má a ṣe ìgbéyàwó musulumi. | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
F0U8E | Mà á lo fìtílà àgbésórí tábìlì láti kàwé. | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
ERQYO | Ṣé o fẹ́ràn láti máa ṣe knotless braid? | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
VAO6L | Yàrá ìbùsùn ni ibi tí a máa ń gbé ìbùsùn sí tí a sì máa ń sún | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
II1GD | Ní ìgbà tí ebi bá ń pa àwọn ọmọdé, wón á bú sí igbe. | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
GTI5O | Ìgbẹ́kẹ̀lé jẹ́ ìpìlẹ̀ ìbáṣepọ̀ ìlera àti ìbáṣepọ̀. | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
HZM4L | Ó kọrin ní ṣọ́ọ̀ṣì lọ́la! | yoruba | female | 30-over | phase 2 | |
4NQNM | Ìlèkùn onigi ti kán. | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
Q7FW1 | Mo ní òògùn ibà oníkóró méjì péré ni kí o lò lánàá | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
Q54MY | Idris ni àwòrán àádọta. | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
Q6KV2 | Awọn oluyọọda ati awọn alabojuto ikẹkọ ni idagbasoke ọmọde wa ni awọn ile awọn ọmọ ti ko ni iya | yoruba | female | 30-over | phase 2 | |
4XT0F | Yóò tó ma ṣiṣẹ́ ní ṣíṣe ni èbúté ọkọ̀ ojú omi | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
4MJ2L | Ṣe o mọ̀ itàn Àmìnà jagunjagun naà? | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
JKNY4 | Adebisi ni ó tà kúlíkúlí náà fún mi. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
82HCV | Iṣu ègé mẹ́ta ni mò ń jẹ. | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
MZLHM | Bọ̀wọ̀ fún Danfari! Ọkùnrin náà wí. | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
2SCF8 | Ìyá mi yóò lọ Guaranty Trust Báńkì lọ́la. | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
LA0Y9 | Malamu náà ta òrùka ìgbéyàwó olówó iyebíye. | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
BNQBX | Ṣé o lọ fún iṣẹ́ àṣewò nínú yàrá àyẹ̀wò físììsì? | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
J8C9N | Ó pàdé Esther ní ilè ìjósìn. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
43FB0 | Bẹ́ẹ̀ni, mo dábẹ́ fún ọmọkùnrin náà lásìkò | yoruba | female | 30-over | phase 2 | |
C2C69 | Tọ́jú ilé àwọn ọmọ aláìlóbi! | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
E9NLH | Mo ti darapọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ àwọn oníròyìn ilé ìwé tí ifáfitì Ilorin. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
K7EWM | Adé yóò bá wọn sọ̀rọ̀ lọ́nà tí kò gbẹ̀fẹ̀! | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
CB5AR | àwọn àgùtàn jẹ́ onísùúrù | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
O0GW8 | Ṣẹ̀ o tẹlẹ̀ mi lórí Twitter? | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
FPAKJ | Ẹranko ẹlẹ́sẹ̀ mẹ́rin tó tóbi ni màlúù. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
43FB0 | Kí ló dé tí ò ń fò? | yoruba | female | 30-over | phase 2 | |
M9HCB | O gbọ́dọ̀ wà ojútùú àdáyébá sí ìṣòro náà | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
4BH1U | Ìlẹ̀kùn tí wọ́n lò yẹn la ma ma lò | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
Q7FW1 | Orí mi ṣí láàárọ̀ fúnṣẹ́ nínú ọkọ̀ àmọ́ mi ò lè ṣíṣe nítorí ẹjọ́ tọ́lọ́kọ̀ bá mi rò. | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
6RQ4Y | Jídé ń ta irinṣẹ́ kápẹ́ntà àti ti ìkọ́lé ní ọjà Ìsìnkàn | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
ZU5PK | Gbé Kọ̀mpútà alágbèéká tí o gbé lọ wá | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
HZM4L | Ìgbàgbọ́ ni wípé àwọn sista ṣìní ìbàlé wọn | yoruba | female | 30-over | phase 2 | |
JKPBW | Ó paálásẹ pé kí ó má fí àtìlẹ́yìn hàn fún ìjọba ológun níbi ìdíje ilé ìwé rẹ̀ | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
GFQXI | Ọ̀la ni òrò ìyàwó tuntun. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
V6MKF | Iyá mi rá ọ̀pọ̀lọ́pọ̀ awọn núdúlù ìfé́ fún mí nígbàtí ó ṣàbẹ̀wò sí New York ní òdún tó kọja. | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
8DNTD | Ṣolá ní bàbá òun ṣe ètùtù airomobi fún òun àti ìyàwó rẹ. | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
DMM7Q | Mo fẹ́ bo ọ̀gẹ̀dẹ̀ dúdú tí wọ́n fún mi títí tí yóò fi pọ́n. | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
OYBT6 | O gbọ́dọ̀ ní onídúró kí o yá owó | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
BOH7B | Yóò ra ìṣó tí ó dára | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
CMYT1 | Ìpele ìbàraeni sòrò láàrin olùkó àti akékòó | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
P73VN | Lọ pé olórí ẹ̀ka ẹ̀kọ́ èdè Gẹ̀ẹ́sì fún mi! | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
XTEFB | Ni diẹ ninu awọn aṣa, obinrin wẹ pẹlu omi oku. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
LR4Z9 | Ẹ̀ka ogun ilẹ̀ Nàìjíríà ní ẹ̀ka mẹ́ta; Ámì Nàìjíríà, ẹ̀ka ogun orí-omi Nàìjíríà àti ẹ̀ka ogun ojú-òfurufú Nàìjíríà. | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
LGUC3 | Adesewa má dàgbà láti dì gbajúmò Olorin | yoruba | female | 18-29 | phase 1 |
Subsets and Splits
No community queries yet
The top public SQL queries from the community will appear here once available.