audio audioduration (s) 0.06 22.7 | speaker_id stringlengths 5 5 | text stringlengths 8 191 | language stringclasses 1
value | gender stringclasses 2
values | age_range stringclasses 3
values | phase stringclasses 2
values |
|---|---|---|---|---|---|---|
PNUGF | Abúlé ni gbogbo àwọn ìlú ńlá jẹ́ tẹ́lẹ̀ | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
WSYC1 | Àwo̩n ewébè as̩alóore mìíràn wà tí a máa ń gbo mu bí i ejìrìn, ewúro | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
1MMFA | Ṣo fẹ́ràn bisikí? | yoruba | female | 6-17 | phase 1 | |
U4OTB | Ṣé wàá gbàdúrà ní aago mẹ́rin ìrọ̀lé | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
417S4 | Ṣẹ́ẹ̀sì jẹ́ eré ìdárayá tí ọ̀pọ̀ ọ̀dọ́ sì máa nífẹ̀ẹ́ sí lọ́jọ́ iwájú | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
77Y1D | Mo máa quiff irun mi fún ayẹyẹ ọjọ́ ìbí mi. | yoruba | female | 6-17 | phase 1 | |
7TZW9 | Ǹjẹ́ Adé ní ìtẹríba? | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
340UT | Ṣé o ka ìwé ìròyìn náà? | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
DU84Z | Ìyá máa ń ran bàbá lọ́wọ́ | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
SE6G6 | Ríí dájú pé ó lọ ogirí nígbàtí ó bá n ṣẹ ọ́njẹ̀ ni ọ̀lá. | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
UZMXA | Àwọn mọ́ṣáláṣí jẹ́ ibi fún ìjọsìn Mùsùlùmí. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
7SK26 | Ọkùnrin ní okó | yoruba | female | 6-17 | phase 1 | |
DY3ZN | N ko le sáré nitoripe ẹsẹ n ro mí. | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
4XT0F | Àwọn ilé-ẹ̀kọ́ kan ń kọ́ àwọn ọmọdé láti borí. | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
BN1ZC | ìdílé a yóò ni ibí ọmọ túntún | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
HZM4L | "Dákẹ́ níbẹ̀", ni sójà náà wí fún olọ́pàá àná yẹn | yoruba | female | 30-over | phase 2 | |
VP87W | Ètùtù ìbúra náà yóò wáyé ní alẹ́ yìí. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
AAFBW | Ṣé o ka ìwé atọ́ni sọ́nà? | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
9QLGC | Awọn ile awọn abirun ṣe pataki isọdọmọ ati iraye si. | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
JCGP7 | A pàrò̩ as̩o̩ ìdámò̩ e̩gbé̩ agbábó̩ò̩lù orílè̩-èdè Nàìjíríà ní bí o̩dún mé̩rin sé̩yìn | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
5TLPT | Ǹjẹ́ ó máa fònfin de èpè ṣíṣe ni ilé rẹ? | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
II8KP | Oyè atọwọda n mú ìlọsíwájú wá ní oògùn àti lilọ oògùn. | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
UND4M | À ǹ ló à. dirọ fun yiyan. | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
L88Q7 | Ọkò òfurufú ń sárẹ́ jú kẹ̀kẹ́ lọ. | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
8AC9O | Ìgbà tí wọ́n ma kérè oko ma tó dé | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
SK1X5 | Ni ìsláàmù, ó máa ṣe àlùwàlá ṣáájú ìrun. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
V6MKF | Adé yóò ṣe irun míìran lọ́dún tó ń bọ̀ | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
XV9FN | Gbogbo ènìyàn tó wà nínú ibùdó ọkọ̀ ojú omi máa jẹ oúnjẹ alẹ́ àpapọ̀. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
KSYPO | Ọ̀kín ni ó rẹwà ju. | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
OJ2WU | Ọ̀pọ̀ àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ni yóò rí ìgbàwọlé sí Politẹ́kíníkì Ìbàdàn. | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
W8MQ2 | Olóòtú ètò ti mo fẹ́ràn láti gbọ́ ètò rẹ̀ ti kú. | yoruba | female | 30-over | phase 2 | |
MOWN7 | Bẹ́ẹ̀ni, èsìn àbáláyé ni bàbá bolu ń ṣe. | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
A5LD3 | Ó gbọ́dọ̀ wá sí sọ́ọ̀sì ní ọjọ́ ìsinmi tí ó ń bọ̀. | yoruba | female | 6-17 | phase 1 | |
MXTT9 | O pọn dandan láti lọ sí ọ̀dọ̀ dókítà lóòrèkóòrè fún àyẹ̀wò. | yoruba | male | 30-over | phase 2 | |
59INZ | Ṣé Nọ́ọ̀sì wà ní ilé ìwòsàn lánàá? | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
2WJTR | Kẹ́mi lọ sí ọjà láti lọ ra Ọ̀tapìàpìà fún ikán | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
BN1ZC | Igbesi aye igboro dagba pẹlu aṣa ati ede alailẹgbẹ rẹ ni igba atijọ | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
5H54X | ibi ìgbọ́kọ̀sí je ibugbe ti a maa n gbe oko si. | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
RIKAN | Àwọn òṣìṣẹ́ ìjọba Nàìjíríà ń fẹ̀yìntì lẹ́nu iṣẹ́ lẹ́ni ọgọ́ta ọdún | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
PYFIU | A lè wo fídíò lórí Facebook. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
Y1CXL | Ipele oyun wo ni o wa bayi? | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
IU1HC | O n'ifẹ bi àwọn agboúnjẹ ṣe gbé oúnjẹ fún-ùn. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
YT0T2 | baba mi, e jẹ ka lo sí zoo | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
9LH7J | Afẹ́sọ́nà ni à ń pe ẹni tí a ń gbẹ̀rò láti fẹ́. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
MBKD5 | Mú mi lòsi ilé iwé àkòbèrè rè | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
43FB0 | Bẹ́ẹ̀ni, mo máa wá sí búkà náà ní ọ̀la | yoruba | female | 30-over | phase 2 | |
EHVQ1 | Bọ ẹran náà fún ìsẹ́jú márùndínlógún. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
3MR4T | Yàrá kọ̀ḿpútà/lab yóò rí àtúnṣe láìpẹ̀ | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
IF56O | wón sé kò bánkì túntùn kàn tí òun jé fideliti bánkì sí àdúgbò wà | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
W8MQ2 | Iná ìrù náà tàn iná Pupa yòò ní ìrọ̀lẹ́ dúdú | yoruba | female | 30-over | phase 2 | |
NM6XG | Atọ́kọ̀se ni bàbáà mi. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
N9GRE | àwọn Igbo nífẹ̀ẹ́ ọbẹ̀ ogbono | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
W8MQ2 | Àwon oun èlò plumber ti a kókó ra nílò kí a sé balùwè tuntun nílé wa | yoruba | female | 30-over | phase 2 | |
FEESO | O gbódọ̀ ra àwọn ohun èlò òṣùwọ̀n | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
MXTT9 | Àwọn Yorùbá á ní "ẹkáàárọ̀" ní àárọ̀. | yoruba | male | 30-over | phase 2 | |
I18DJ | Bẹ́ẹ̀ni, ìṣù ewùrà ni. | yoruba | female | 6-17 | phase 1 | |
3TUIS | Masaa máa ṣàkóso lórí ìgbáradì ogun àti àwọn ohun èlò ogun | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
LA0Y9 | Àwọn ọmọ ilé-ẹ̀kọ́ gíga lọ sí ìrìn-àjò afẹ́ | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
Q54MY | Màá pa àwọn aláǹgbá náà ní ọ̀la | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
A7A2R | Àpò Ẹ̀wà mẹ́fà ni bàbá mi rí nínú irè oko wọn | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
Q7FW1 | Wọ́n já owó mi ní báńkì láì ṣe ìdúnadúrà kankan | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
KY5I7 | Bá mi pe obinrin aláró dídà yẹn. | yoruba | female | 30-over | phase 2 | |
ELC7E | Àwòn fiimú itán sàbá mà n kó ni lèkò | yoruba | male | 30-over | phase 2 | |
KDXVX | Bẹ́ẹ̀ni, orúkọ àdúgbo náà nìyẹn | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
X0LB4 | Ṣé a ti kéde ẹni tí ó jáwé-olúborí? | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
ZLOOP | Ní ọdún díẹ̀ sẹ́yìn , ni wọ́n dín ẹyin díndín tí ó tóbi jù lo ní ìlú lágbàáyé | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
XOYTO | Ní àtijọ́, àwọn àgbà wá máa ń gbàdúrà pẹ̀lú ọtí àti obì | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
0X4MG | Amà ń se Ìgbẹyàwó lẹkan nigbe sí àyé ẹyan. | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
8RSV0 | Ọkùnrin náà yọ aṣọ ìsomọ́ọ̀dí ìkókó náà. | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
NUP61 | Ilé iṣẹ́ íńdómì wà ní Nàìjíríà. | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
GP6G0 | Njẹ́ àwọn ọmọ náà yóò ta eré-lúdò lọ́ la? | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
7TZW9 | Jósẹ́fù gba ìre ìkeyìn ẹnu bàbá rẹ̀ | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
92JZ4 | Èmi yóò yá owo láti awọn bánkì ìya owo ilé. | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
OVFI5 | Lọ bámi ra àpò ìresì wàá! | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
UYF58 | Nigba wó ló fẹ̀ pà éwùrè yèn? | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
AGXXX | Bàbá àgbà sọ Ìtàn ìgbaànì fún wá ní alé àná. | yoruba | female | 6-17 | phase 1 | |
X0LB4 | Ṣe ìpàdé pẹ̀lú akọ̀wé owó ní ọ̀la | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
2SCF8 | Ọ̀pọ̀ àwọn ọkùnrin Mùsùlùmí ni wọ́n máa ń fẹ́ ìyàwó púpọ̀. | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
43FB0 | Obìnrin kìí fojú rí orò | yoruba | female | 30-over | phase 2 | |
JS59W | A lọ sí ọgbà ìyá mi láti kó àwọn èso tuntun. | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
HNSNF | pe o jẹ oniṣiro kò túmọ sí wípé o ṣiṣẹ ní ilè ìfowópamọ́ | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
LCVX8 | Àwọn òbí ọmọbìnrin to fẹ́ ṣe ìyàwó ló máa ń ṣe eto ayẹyẹ idana | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
HNSNF | Obìnrin yẹn tá aṣọòkè fún ìyá mi. | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
NNEZM | Ṣé Èkó ni ò ń lọ? | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
V6MKF | Gbogbo nìṣe wúlò fún ara | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
0KQA0 | Mo lọ ṣe àfikún orúkọ ọkọ mi sí orúkọ mi ni ilé ẹjọ́ | yoruba | female | 6-17 | phase 1 | |
W8MQ2 | Ọkùnrin náà ra parasítámọ̀. | yoruba | female | 30-over | phase 2 | |
7TZW9 | Ṣé Òòṣà kọ́ ló lọ yàrá àwọn olùkọ́ | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
IJ4DB | Kamẹrúùn yan ìṣèjọba olómìnira | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
OVFI5 | Ọkọ rẹ̀ fẹ́ ìyàwó méjì le | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
L88Q7 | Olórí ẹlẹ́sìn ìgbàgbọ́ ni Pásítọ̀ | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
FCLZH | Ta ni ò ń bá jáde lónìí? | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
P28CN | Nu pátákó ! | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
VQHMV | O ò gbọdọ̀ ṣe èké mọ́. | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
Z4L9W | Ṣó ń tẹ́lẹ̀ ẹ jáde ní? | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
AYARU | Rárá, o ò lè fi asàn wẹ́wẹ́ sínú àgbo jẹ̀dí | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
DHGUM | Mẹ́wàá ni mo máa rà. | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
4OOC9 | Ọkọ̀ èrò ní wón fí kò àwọn èrò | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
9YHFQ | Olùkọ́ mi sọ èsì ìdánwò fún mi laana. | yoruba | male | 6-17 | phase 1 | |
18W0W | Aṣojú ìgbààyèsílẹ̀ kan ń ràn Dayọ̀ lọ́wọ́ láti gba ààyè ọkọ̀ òfurufú sílẹ̀. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 |
End of preview. Expand in Data Studio
README.md exists but content is empty.
- Downloads last month
- 19