Dataset Viewer
Auto-converted to Parquet Duplicate
audio
audioduration (s)
0.06
37.4
speaker_id
stringlengths
5
5
text
stringlengths
2
194
language
stringclasses
1 value
gender
stringclasses
2 values
age_range
stringclasses
3 values
phase
stringclasses
2 values
IF56O
Awòn óbìrín sé pàtákì làwújò
yoruba
female
18-29
phase 2
MGWAM
Ọmọdé tí ó bá máa mọ ọwọọ́ wẹ̀, á bá àgbà jẹun
yoruba
female
18-29
phase 2
WJXIT
Òjò wó ni ájòyò igbéyàwó Olabisi?
yoruba
female
6-17
phase 1
II8KP
Chike dojú kọ ẹ̀sùn ìwà ọ̀daràn tó lágbára ní ilé ẹjọ́.
yoruba
female
18-29
phase 2
M9HCB
O gbé pọ́npọ́n náà sì èjìkà.
yoruba
female
18-29
phase 1
QLGXT
Epo Pupa gbona máa ń ṣíṣe fún ikọ.
yoruba
female
18-29
phase 1
GSS7E
Rárá, mi ò rí ewédú rà nígbà tí mọ lọ sí ọjà.
yoruba
female
18-29
phase 1
WS53N
Lọ kẹ́kọ̀ọ́ ní ẹ̀ka ìmọ̀ sáyẹ́ǹsì!
yoruba
female
18-29
phase 1
RIA0Z
Awọn Labalaba ni iye ti yoo rẹwa
yoruba
female
18-29
phase 1
TOZM7
Ninu itan, iran Ada jẹ ẹrú
yoruba
male
18-29
phase 1
ZHR4X
Mo gbọ́dọ̀ sọ fun kó wá sí Dùbàyí
yoruba
female
18-29
phase 2
4NKV8
Ìdílé náà gbà ẹbùn síbí títún.
yoruba
female
30-over
phase 1
QG4N9
Nkọ fẹ́ rí ẹ̀ ní tó sí ilẹ̀ mi!
yoruba
female
18-29
phase 1
D3RSB
Ìyá mi sọ fún mi pé, Òdùduwà lọba àkókò ti Ìlú ńlá Ifẹ̀
yoruba
female
18-29
phase 1
KONPA
Ọmọbìnrin Hausa náà wá gba tumfafiya
yoruba
female
18-29
phase 1
II8KP
Kólónẹ́ẹ́lì jẹ́ ipò kan ní ẹ̀ka ogun.
yoruba
female
18-29
phase 2
43FB0
Ta ni wọ́n sọ fún pé kí ó máa jẹ ọbẹ̀ ewuro ní gbogbo ìgbà?
yoruba
female
30-over
phase 2
II8KP
Ile-ifowopamọ ìṣòwò fún awọn ènìyàn lawin .
yoruba
female
18-29
phase 2
7TZW9
Kọ́lá ń ta èso ní òyìngbò.
yoruba
male
18-29
phase 2
IF56O
talo ba ẹrọ omi ilé iwe je?
yoruba
female
18-29
phase 2
WC31P
Mariam ni asọ wiwẹ ni gbogbo ori é.
yoruba
female
30-over
phase 1
2SCF8
Wa kombu to dara fun irun ori rẹ!
yoruba
female
18-29
phase 2
OVFI5
GRA jẹ́ ọ̀rọ̀ tí a máa ń lò ní Èkó àti àwọn ẹ̀ka orílẹ̀-èdè Nàìjíríà mìíràn.
yoruba
female
18-29
phase 2
OHF09
Ṣé Bọlá ń dirun?
yoruba
male
18-29
phase 1
SRYA7
Adé máa kọ ọmọ rẹ ni ìwà rere.
yoruba
female
18-29
phase 2
O4L4N
Ẹnìkan péré ni a máa ń yàn gẹ́gẹ́ bí àdénì.
yoruba
female
18-29
phase 1
GL6QE
Amúnilásífo ọrọ èràn ùbíye
yoruba
female
30-over
phase 1
1M882
Adarí ilé iṣẹ́ náà ṣàfihàn ẹ̀ka ọ́fíìsì fún àwọn oníbàárà.
yoruba
female
18-29
phase 1
2PK17
Ra ẹja panla lati oko ipeja ni ọla
yoruba
male
18-29
phase 1
MPUZO
Àwọn iṣẹ́ ṣíṣe àwùjọ jẹ́ àwọn iṣẹ́ ṣíṣe tí ó jọmọ́ ti àwùjọ
yoruba
male
30-over
phase 1
FQ192
A ò ṣe àwọn ẹ̀rọ ìdáná láti mú iná dídá rọrùn lọ́jọ́ wájú
yoruba
male
6-17
phase 1
NJEWX
Sọ tí ra àdàbà yẹn?
yoruba
male
30-over
phase 1
JPV0A
Àwọn ọdẹ ni Yorùbá máa ń sin òkú ọ̀kan lára wọn sínú aginjù.
yoruba
female
6-17
phase 1
DJ3BB
Àwọn èèrà máa ń rá ní ìlà kan.
yoruba
female
18-29
phase 1
4N1TL
ṣé o fẹ́ràn wásapù ju fesibúkù lọ?
yoruba
male
30-over
phase 1
VAO6L
Bẹ́ẹ̀ni, òní ni àjọ̀dún ìdásílẹ̀ ìjọ naa
yoruba
male
18-29
phase 2
LENVB
Wálé ṣàbẹ̀wò ilé ìtura náà fún ọjọ́ mẹ́ta ní ọ̀sẹ̀ tó kọjá
yoruba
male
18-29
phase 1
O0GW8
Idíbò̀ odún tó kọja tí kún fún ìwà ìbájẹ́.
yoruba
male
18-29
phase 2
5F2BA
Ṣé wọ́n ń jọ́sìn òrìṣà náà?
yoruba
female
18-29
phase 1
LRMKP
Child marriage is not allowed in many countries
yoruba
male
30-over
phase 1
4XT0F
Á lọ ra ẹrù ọmọ ní ọjọ́ ìsẹ́gun tí ó ń bọ̀
yoruba
female
18-29
phase 2
NGK6O
Iyọ̀ díẹ̀ ni mo fi sí ọbẹ̀
yoruba
male
6-17
phase 1
AIR0P
Bẹẹni, Emi yoo ṣeto selifu iwe daradara
yoruba
female
30-over
phase 1
1OK1H
Òfin wà to dé gbogbo eré ìdárayá.
yoruba
female
18-29
phase 1
X9656
Àwọn yóò máa lu etí tó ju ọ̀kan lọ
yoruba
female
18-29
phase 1
KY5I7
Ìyá ìyá a mí ṣi ń dá owó sí ọwọ́ alájọ́.
yoruba
female
30-over
phase 2
F9VON
Láti ara ọsàn ni a tí ń rí omi ọsàn.
yoruba
female
18-29
phase 1
OVFI5
Ó ń kọ́ ilé ìtura rẹ̀ lọ́wọ́
yoruba
female
18-29
phase 2
HWEYQ
Irú ẹ̀fọ́ kan ni píìsì jẹ́
yoruba
female
6-17
phase 1
E7IR1
Ṣé bàbá rè je ìrẹsì lánà?
yoruba
female
18-29
phase 1
DZP74
Ọmọdé tí ó wà ní ọmọ dún tó kéré sí ọdún mẹ́wàá yóò wà ní ilé ẹ̀kọ́ alákòbẹ̀rẹ̀.
yoruba
male
18-29
phase 1
6UQ9S
Mo máa lọ ìpínlẹ̀ mẹ́wàá ni Nàìjíríà.
yoruba
female
6-17
phase 1
II1GD
WhatsApp dára fún ìbásọ̀rọ̀ tó yá.
yoruba
male
30-over
phase 1
KSYPO
Ìlànà ìjọba alágbádá ni orílẹ̀ èdè Nàìjíríà ń lò
yoruba
female
18-29
phase 2
J2FOU
Pàrọ̀ ẹnu ìgẹrun náà!
yoruba
female
6-17
phase 1
43FB0
Ṣé wà á jẹ àlùbọ́sà yìí?
yoruba
female
30-over
phase 2
HPTGN
Amina, ṣajọpọ iṣẹlẹ ikojọpọ fun awọn aini ile ni oṣu ti n bọ
yoruba
female
18-29
phase 2
C2C69
Gba ọsàn kó mu!
yoruba
female
30-over
phase 1
3RZ6T
Ìyá Bólú se ọbẹ̀ ilá lọ́sẹ̀ tó kọjá.
yoruba
female
18-29
phase 1
NHXYV
A ṣubú lórí ọ̀kadà nígbà tí à ń lọ sí sọọsi.
yoruba
female
30-over
phase 1
KSYPO
Iṣẹ́ ẹ kí wọ́n kawó ni wọ́n gbà
yoruba
female
18-29
phase 2
ELC7E
Ṣe o sun lori ibusun yẹn?
yoruba
male
30-over
phase 2
DBKQL
N jẹ́ o ni láti ra àwon oun kan kan fun ìgbádùn yàrá ibùsùn ?
yoruba
male
18-29
phase 1
IU7RH
Ìyẹ̀rẹ̀-ifá ni àwọn babaláwo máa ń pè
yoruba
male
30-over
phase 1
8HJAE
Má ṣe lọ parasítámọ̀ ní àlòjù.
yoruba
female
30-over
phase 1
WPMD0
Ìlànà oúnjẹ sísè méta ni mo mọ̀.
yoruba
male
6-17
phase 1
OVFI5
bá mí rà garawa títún
yoruba
female
18-29
phase 2
HZM4L
Ẹ máa fòpin sí ìpara ẹni yìí.
yoruba
female
30-over
phase 2
K3VHU
Ẹsẹ̀ ọmọdé yìí kò tíì ranlẹ̀ daindain
yoruba
female
18-29
phase 1
HZM4L
Bẹ́ẹ̀ ni, ó kó lọ Ìkòyí.
yoruba
female
30-over
phase 2
2WJTR
Ṣe ma jẹ́ ọ̀rẹ́ ?
yoruba
female
18-29
phase 2
VFKYO
Ikú dájú gidi gán
yoruba
female
30-over
phase 1
GNNQV
Okowò ilé oúnjẹ jẹ́ èyí tó pẹ́ ní Èkó.
yoruba
female
18-29
phase 1
CKKGY
Ọ̀pọ̀ àwọn ohun-èlò nínú ilé ni ó ń lo iná ẹ̀lẹ́tíríkì.
yoruba
male
30-over
phase 1
3CDW5
Awọn oluduro ni awọn ibi isere wọnyi ṣe iranlọwọ fun awọn alabara ati gba awọn aṣẹ daradara
yoruba
female
6-17
phase 1
DD75D
Ṣé yíyan nǹkan wọ́ pọ̀ ní ayé àtijọ?
yoruba
female
30-over
phase 1
Z7RNA
Lagata ló n tá igbó ninú àbètè yèn
yoruba
female
30-over
phase 1
2PK17
Ajoke n ba awon omo iyawo baba re ja lana.
yoruba
male
18-29
phase 1
TMNER
béèni ajá tí jẹ́un lóni.
yoruba
male
18-29
phase 1
JNYOA
Àwọn osise ijọba ṣe ètò ijọba àti ìmúṣẹ rẹ̀ dáradára
yoruba
male
30-over
phase 1
RRRYG
Dókítà ojú fún Bimpé lóògùn ojú fún ojú rẹ̀
yoruba
female
18-29
phase 1
QBWT6
Àwọn ọkọ òfurufú má ń bà sí pápákọ̀ òfurufú Muritala Muhammad ní Ikeja ni ìpínlẹ̀ Èkó
yoruba
male
18-29
phase 1
QGIVU
A sọ fun wa lati ra eraser tuntun kan
yoruba
female
30-over
phase 1
OTSUA
Awọn ohun ọgbin Kofi Nganda gbilẹ ni oko
yoruba
female
30-over
phase 1
0ETOK
Dírayà máa ń wà ní ilé ìdìrí.
yoruba
female
6-17
phase 1
KJZZS
Àwọn ọmọ yín ti fọ́ dígi ńlá yẹn
yoruba
female
30-over
phase 1
O0GW8
Títi sọ́ pé wọn yóò lọ sí ọ̀jà ni ọ̀ṣẹ̀ tó nbọ̀ láti rá àwọn orúkà
yoruba
male
18-29
phase 2
205LN
Ìlú Àkúrẹ́ yóò jẹ́ ibi tí yóò máa gbòòrò pẹ̀lú àwọn ilé titun àti àwọn òpópónà tó dijú lọ́jọ́ iwájú.
yoruba
male
18-29
phase 1
XLFVK
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ olódodo ló ń jìyà ẹ̀sẹ̀ àìmọ̀
yoruba
male
18-29
phase 1
Z2EVY
Bẹ́ẹ̀ni, mo ti fi ẹjọ́ arákùnrin abánisẹ́wò tó fún ọ ní owó pánda náà sùn
yoruba
female
18-29
phase 1
GCUI4
Inú ń bí Laura nígbà tí ó gbọ́ àwọn gbọ́yìísọ̀yìí nípa ọ̀rọ̀ ayé rẹ̀.
yoruba
female
6-17
phase 1
JDOLK
Onífèrè máa débí láìpẹ́.
yoruba
female
18-29
phase 1
03GAR
Iná iwájú kẹ̀kẹ́ náà yóò tàn bí ọ bá ń se tẹ pẹ́dà
yoruba
male
18-29
phase 1
71XDU
Manugoro ti máa ń somi jù.
yoruba
male
18-29
phase 1
5BMW7
Àwọn òpó ayélujára ń ṣẹ̀dá ọ̀pọ̀ ibi ju ire lọ.
yoruba
female
6-17
phase 1
7EUJY
A lè fi ewé làálì ya àwòrán sí ara
yoruba
female
6-17
phase 1
0C0M3
Tẹ̀lifísàn ti di ọ̀wọ́n gógó lọ́jà
yoruba
female
30-over
phase 1
LRPZH
Ọbẹ̀ náà sọ lórí iná fún ìṣẹ́jú mẹwa.
yoruba
male
30-over
phase 1
J1RGK
Dọ́kítá náà yóò dé ní ago mẹ́ta ọ̀sán.
yoruba
male
18-29
phase 1
J1RGK
Dọ́kítá máa ń ṣiṣẹ́ ní ilé-ìwòsàn.
yoruba
male
18-29
phase 1
End of preview. Expand in Data Studio
README.md exists but content is empty.
Downloads last month
21