audio audioduration (s) 0.06 28.9 | speaker_id stringlengths 5 5 | text stringlengths 6 179 | language stringclasses 1
value | gender stringclasses 2
values | age_range stringclasses 3
values | phase stringclasses 2
values |
|---|---|---|---|---|---|---|
MOLZM | Tani alága ìpolongo ẹgbẹ́ òṣèlú tí Kọ́lá wá? | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
QJ6H7 | Díẹ̀ nínu awọn àṣà ní Nàìjíríà rí awọn ìkà ìkà ìkà. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
G4GLL | Tani wọ́n n fi ajá bọ nínú àwọn òrìsà? | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
II8KP | Orin ifẹ kò jẹ orin ìbànújẹ | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
V6MKF | Rárá, ẹ̀mi kíí yọ̀ò darapọ̀ mọ́ ẹka tuntun ni igba ikàwé àtẹ̀lẹ | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
IKZHA | bẹ́ẹ̀ni, àpèjẹ kérésìmesì ti ilé ìwé náà dùn | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
DK6N8 | Gbé ẹrù rẹ kí o tẹ̀lé lọ sí ojúbọ | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
AMRIF | Ọkùnrin le ní ìyàwó púpò nínú olobinrin púpọ. | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
KSB4Q | Ogo afikpo náà wáyé fún oṣù kàn. | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
SCMQD | Mo máa tún ọ̀kadà mi kùn. | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
EG4SI | Olùdarí náà wípé kí won pàrọ̀ kámẹ́rà náà. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
JNHHS | Dọ́kítà yìí ní ka ra oògùn ikọ́ cofflin fún Túńdé. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
OZCG2 | Gbogbo ju iye; fi omi pamọ fun ojo iwaju | yoruba | female | 30-over | phase 2 | |
MGWAM | Mo fi ẹyin ẹyọ kan tókù ṣe chin chin | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
OZCG2 | o ni anfani tẹẹrẹ | yoruba | female | 30-over | phase 2 | |
HH0CR | Olú já Ewedu náà | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
UGPLR | Ṣé ẹsẹ̀ Ẹlẹ́dẹ̀ sanra? | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
ZNH22 | Mo ra ẹ̀rọ ìdáná oníná lọ́sẹ̀ tó kọjá. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
BN1ZC | Awọn aṣọ ile-iṣẹ iṣẹ yoo di gbowolori fun eniyan | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
0UH34 | Ṣé o won bí aṣọ náà ṣe gùn tó? | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
OVFI5 | Báwo lo se rò pe isẹ́ ìkọ́lé yio rí ni ojó iwájú | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
DK6N8 | Níbo ni ọdún ìbejì náà tí ń ṣẹlẹ̀ | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
1O7ZA | Wọ́n á ṣe iṣẹ́ abẹ ọ̀nà ọ̀fun fún un láti wòsàn | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
V6MKF | Títí yọọ̀ rà awọn gílòbù iná ni ilẹ̀ itajà ni ọlá | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
S24CX | Atọrọjẹ kì í yó. | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
K3KLM | Ilé ìtajà náà yóò ní sìgìdì tó ń kí ni. | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
MXTT9 | Eré ìje náà, tí ó ń wáyé lọ́dọọdún, máa ń fa àwọn eléré-ìdárayá láti àwọn agbègbè tó wà nítòsí. | yoruba | male | 30-over | phase 2 | |
J1KV0 | Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ènìyàn tó ń gbé ní ìpínlè Kwara jẹ́ Yorùbá | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
APQO2 | Ṣé Báyọ̀ ó mú àgé wá làárọ̀? | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
LET8H | Rárá, mi ò jẹ́ núdùsì pẹ̀lú ẹyin | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
VKW4W | a gbọdọ gbọ orin iremolekun tirẹ. | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
OYBT6 | O máa tún owó yìí kà fún mi ní ọ̀la | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
WUSNO | Yàrá ìkàwé wà fún oríṣiríṣi ìpele ní ilé ìwé alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ . | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
O0GW8 | Páàkì ọkọ̀ rẹ níìsín! | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
JDIDU | njé Tope yíò dì ìyàwó Fola ? | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
CS3YA | Wàá se oúnjẹ fún mi lọ́la. | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
W8MQ2 | Ẹ̀kùn náà á bí mọ́ ní ìparí ọ̀dún. | yoruba | female | 30-over | phase 2 | |
O6E7Y | Bẹẹni, Alani sun lo | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
7LN7A | Ẹ̀kọ́ ìjọ ti fi ìlànà lélẹ̀ fún àwọn olùsìn | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
MZLHM | Ni ayé àtijọ́ gbogbo ọjọ́ ni àwọn baba ńlá wa fi máa ṣiṣẹ́ | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
Q7FW1 | Mo ni lati pin ijoko eyi ti o yẹ ki o gba nikan kan ero | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
HVEP1 | Tade máa lọ sí ilé ìwé lórí kẹ̀kẹ́ rẹ̀. | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
VAO6L | Ìgbà wo ni ọjà èso? | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
ELC7E | Dayo lórúkò òkúnrin tó n jè óyé yèn | yoruba | male | 30-over | phase 2 | |
G1ERL | Arábìnrin Adepoju ti n kọsẹ irun gígé. | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
LNXWF | A ko le fun ọmọ ni akọle | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
AA6NB | Bẹ́ẹ̀ni, wón ti jagun rí. | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
J8C9N | Ó ń ná owó lórí ajílẹ̀ nítorí ó ń lọ ilẹ̀ kan ṣoṣo fún ọ̀gbìn. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
P73VN | Ilé ìjọsìn méjì ni a ní nínú ọgbà kọ́lẹ́ẹ̀jì wa | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
O4Q43 | Emi ko ri orúkọ mi nínú ìwé oríṣiríṣi. | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
UJXXA | Olú kú àsẹ̀yìndè ìyá rẹ | yoruba | female | 6-17 | phase 1 | |
MF6K9 | Olùtọ́jú ilé ìtajà ló máa ń rí sí títún ilé ìtajà ṣe. | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
MXTT9 | Mo gbé ìwé-ìròyìn tó wà ní orí tábìlì rẹ̀. | yoruba | male | 30-over | phase 2 | |
V6MKF | Lọla wà níbi ilé-ẹjọ́ náà | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
XAVV1 | Kẹ́mi yóò gbéra lọ sí ìlú Zanzibar ní orílẹ̀ èdè Tanzania fún ẹ̀kọ́ rẹ̀ ní oṣù tó ń bọ̀ | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
VPH1J | Ó yẹ kí àwọn olùrànlọ́wọ́ máa ṣe ìrànwọ́ fún àwọn olùkọ́ | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
OVFI5 | ẹ̀sùn ìpànìyàn ni wọ́n fi kàn án. | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
MZLHM | Ojo máa wà ní ibi ìkàwé ní agogo mẹ́rin | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
TGB73 | Ìtàn ni a sọ nígbà gbogbo pẹlu ọ̀rọ̀ láìdakẹ | yoruba | female | 6-17 | phase 1 | |
ZXO3P | Ṣé oníbárà yin ni túnjí ni ofíìsì? | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
SGO1V | Arábìnrin yẹn àti òfófó ti di ọ̀rẹ́. | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
NAVZP | Títí ń jẹ oúnjẹ gẹ́tò | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
HKH36 | Ilé alájà akọkọ ní Nàìjíríà wa ni Badagry. | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
2SCF8 | Ní àkókò ooru to kojá lo, a ṣiṣẹ́ àtúnse lára ilé níbití a tilo orísìrísì oun élò ìkólé | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
O4HRQ | Bàbá mi jẹ́ bàbá tó ń dúró sílè. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
HKJNT | Nílẹ̀ Yorùbá láyé àtijó, ọkùnrin a máa wọ ṣòkòtò kẹ̀m̀bẹ̀, bùbá àti fìlà abetí-ajá | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
2OU1D | A ò ní ra ẹja náà ní ilé ìtajà náà tí ó bá tí ń bàjẹ́ | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
CSMDP | Sé ó dára kí a dá abẹ́ fún ọmọ ọkùnrin. | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
B3XQB | Rárá, èmi kọ ní mo jẹ búrẹ́dì | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
MXTT9 | Wọn kì í jẹ oúnjẹ gidi ní ẹ̀wọ̀n | yoruba | male | 30-over | phase 2 | |
S35UB | Ọjọ ẹti ni ọjọ ijọsin awọn músúlúmì | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
BN1ZC | Olùsirò náà yóò wà ní ọ́fìsì rẹ̀ ní ọ̀la | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
43FB0 | Ǹjẹ́ wà á fún Bọ̀dé ní ìwé mẹ́rìnlélẹ́ẹ̀dẹ́gbẹ̀ọ̀kànlá? | yoruba | female | 30-over | phase 2 | |
P1UBQ | Igi pò nínú igbó. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
OZCG2 | o tèté jí láti yàgò fún súnkèré-fákérè | yoruba | female | 30-over | phase 2 | |
LFHS5 | Ṣé ẹ kò omo àgùntàn wọ ilé ni àná? | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
YH50Q | Mo lọ ẹ̀pà mọ́ oúnjẹ ìkókó mi. | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
KONPA | Ó lo kànkàn onírin láti bó ìkòkò náà | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
BN1ZC | Oúnjẹ tó dáa ni wọ́n ń tà láwọn ilé oúnjẹ tó wà lápá ọ̀tún | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
A5LD3 | O gbúdò se ìbánikẹ́dùn àti àdúrà fún olóògbé nísinsìnyì | yoruba | female | 6-17 | phase 1 | |
59INZ | Wọ́n ń gbé òponá tuntun bọ̀ lọ́sẹ̀ tó ń bọ̀ | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
4NQNM | Ìjọba nílò láti tún àwọn yàrá ìkẹ́kọ̀ọ́ kan ṣe | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
HPTGN | Bawo ni awọn ohun elo ọmọ to ti ni ilọsiwaju bi iyọ iyọ ati awọn nkan isere tuntun yoo ṣe apẹrẹ itọju ọmọde ati ere idaraya ọjọ iwaju? | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
PLW8F | Oògùn ìtọ̀ ṣúgà máa ń fa ara sísan. | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
5TLPT | Ṣé o máa da ọṣẹ ìwẹ̀ rẹ sínú ẹ̀rọ ìbọṣẹ ìwẹ̀? | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
JC6UM | Níbo ni o tí ra àdí àgbọn? | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
6ZTSE | Ṣájà rẹ̀ gan mọ inú sọ́kẹ̀tì ògiri | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
DK6N8 | Mi ò sí ní ayẹyẹ Ọ̀ṣun Òṣogbo ní ọdún tó lọ | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
TVU3E | Ọkọ ojú irin láti Èkó dé Abẹ́òkúta tí kò fa súkere lójú òpópónà | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
UVCNW | Mo wípé kí o yàgò fún ìwà àbòsí | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
ESYP3 | Olú sọ gbogbo ṣíbí inú ìyàrá-ìdáná nù. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
BAD8C | Padà lọ mú àwọn ọmọ wá ní ilé-iwé | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
MW6M5 | Mo ní kí o fi ẹ̀kú egúngún han ọmọ náà | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
TGB73 | Ìwé ìtàn ti àlùpàídà jẹ kikọ nìpasẹ̀ Chris Colfer. | yoruba | female | 6-17 | phase 1 | |
VA1ZO | Bẹ́ẹ̀ni, mo ún gbé oúnjẹ wọn bọ̀ | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
59INZ | Báyọ̀ sọ pé òun kọ́ àwọn ẹ̀kọ́ púpọ̀ nínú ìtàn Ìjàpá àti ajá | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
ELC7E | Sò itán álò ti mó pá fún è lòsè tó kòjá | yoruba | male | 30-over | phase 2 | |
NSOXE | Iye owó ríra ọkọ̀ alùpùpù tí ga sí i. | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
VAO6L | Rárá,Bọ́lá kò le jẹ awùsá ní ọ̀sán. | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
KY5I7 | Mo se Ìrẹsi jọ̀lọ́fùú náà ní àná. | yoruba | female | 30-over | phase 2 |
End of preview. Expand in Data Studio
README.md exists but content is empty.
- Downloads last month
- 21