audio audioduration (s) 0.06 27.6 | speaker_id stringlengths 5 5 | text stringlengths 7 180 | language stringclasses 1
value | gender stringclasses 2
values | age_range stringclasses 3
values | phase stringclasses 2
values |
|---|---|---|---|---|---|---|
UZMXA | Ọ̀pọ̀ aṣọ ni wọ́n ṣé láti ẹ̀gbọn òwú | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
I9T60 | Ile naa kun fun ẹrin awọn ọmọde. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
9HYXA | Bẹ́ẹ̀ni ẹlẹ́sìn ìbílè ni bàba bàbá mi | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
1NZYL | Ádárì ètò ìdárayá máa ń wà ní ilé ìwé sẹ́kọ́ńdírì. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
UZ6RK | Ọlá mọ nípa àṣírí ẹgbẹ́ náà. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
KSYPO | Mo fẹ́ lọ sí Sọ́ọ̀sì lọ́jọ́ àìkú tó ń bọ̀ | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
0ATFV | Babajide n lò si òdò iyá rè lòlá | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
43FB0 | Ta ni ó ń ṣiṣẹ́ ní ibùdó ọkọ̀ ojú omi? | yoruba | female | 30-over | phase 2 | |
59INZ | Mà á ṣebòlò lọ̀túnla | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
UVHS4 | Ilé oúnjẹ ìgbàlódé máa ń ta ohun mímu pẹ̀lú oúnjẹ wọn | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
HN1Q2 | Lọ sí Dìpátímẹ̀ntì ẹ̀kọ́ orin níìsín! Olùkọ́ ilé-ìwé gíga naa pariwo | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
6UQPG | Aṣọ ti a ṣeto ohun ọṣọ ati awọn atilẹyin ti o nilo fun fiimu naa | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
5E7GR | Ọgbẹni Jàkọbì tì jẹ olúyẹwo owó wà fún ọpọlọpọ ọ̀dún. | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
GSS7E | Rara, ao je ewedu loni. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
GZ44W | Gáàsì tí ó fín dáná rẹ̀ ti tán | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
W8MQ2 | Aṣọ̀ ikèlè-iwé tó yà òṣì yẹ̀ kí Árẹ̀mú párọ̀ rẹ. | yoruba | female | 30-over | phase 2 | |
HPTGN | Awọn ayẹyẹ ibi ṣe ayẹyẹ dide ti awọn ọmọ tuntun, ti samisi titẹsi wọn sinu awọn awujọ atijọ | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
ZLOOP | Ki ọba! Bashorun pàṣẹ. | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
0C4JJ | bó ago yén ní wón pàṣẹ fún | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
W8MQ2 | Ahán ní a fí ń mọ àádùn oun kan. | yoruba | female | 30-over | phase 2 | |
SRYA7 | Ìfọyín ìgbàlódé dára gan-an | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
2WJTR | Ṣé o n bá nọ́ọ̀sì sọ̀rọ̀? | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
HNSNF | Wọ́n gbá ọmọkùnrin náà lórí ẹ̀rọ ayélujára. | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
E69XO | Báwo lo ṣe fẹ́ fo gbogbo erò yìí?? | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
PWGAW | Lọ máa gbàdúrà! | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
2WJTR | Òṣù tí o ń bọ̀ ní wọ́n sún ìgbẹ̀jọ́ náà sí. | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
ZLOOP | Ṣe o rá akojọpọ combu tuntun? | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
0ZPS6 | Lọ si bursar lẹsẹkẹsẹ | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
HNSNF | Àwọn anulẹ̀ tún vblgbo yunifásitì ṣe lánàá. | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
I4LNP | Ó fẹ́ràn láti máa lọ sí patí lọ́jọ́ àìkú | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
9LH7J | Àwọn ará Oyo yóò ṣètò ayẹyẹ ìkíni fún àwọn àlejò | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
Z6OOO | Irin ájó òlà á kúrú | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
ISX47 | Mo gbó̩ pé ìyàwó Tádé ti bímo̩ è̩ke̩fà | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
0MK2U | a ó nílò omi tí ó tó láti po yẹ̀pẹ̀ ní ọ̀la. | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
3FTWU | Bàbá Bọ̀dé yóò fọ eyín rẹ̀ lálẹ́. | yoruba | female | 6-17 | phase 1 | |
CYCYS | A o lọ sí ọ̀dọ àwọn ònkọlà lọ́la | yoruba | female | 6-17 | phase 1 | |
BXQ9S | Àwọn ọmọ iṣẹ́ káfíńtà máa ń tẹ̀le lọ ṣiṣẹ́ | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
CB5AR | Ṣe o ko ra chinchin lana? | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
UP4RQ | Kódá ki mòtó má sáré àsájú | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
VAO6L | Ñjẹ́ o máa ra ìpanu fún mi ní ọ̀la? | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
CCO6H | Àkókò kérésìmesì jẹ ìgbà ayọ. | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
1KRXX | Àpọ̀jù mekọọ̀pù ti jẹ́ kí ojú Àmọ̀kẹ́ ó rí rásuràsu | yoruba | female | 6-17 | phase 1 | |
Q7FW1 | Mo ti wo ere na. | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
F44ZV | Ṣé Kúnlé ń ṣe fàájì ní ilé ọtí? | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
Q6KV2 | Ṣé awakọ̀ náà ti yó ni? | yoruba | female | 30-over | phase 2 | |
JKNY4 | Adekemi ṣẹ̀dá isẹ́ amọ̀ tó rẹwà jùlọ ni abúlé. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
XEMXP | Àwọn gómìnà tí gba yàrá ọlọ́lá tán | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
8C1U5 | Àwọn agbábọ́ọ̀lù ń ṣe ìgbáradì lórí pápá ìṣeré | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
IF56O | Nibo ni o ti ṣiṣẹ? | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
II8KP | Ṣé ìwọ ni òun lo àáké-ìmú-ǹkan mi? | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
XNYAV | Ma ṣe gba Ìṣèjọba Anìkanpàṣẹ laaye! | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
DDY19 | Mararaba ti jẹ iṣẹ akanṣe lati ni idagbasoke ilu pataki ni awọn ọdun to nbọ | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
L58T5 | Bẹ́ẹ̀ni, o le ra ẹran lati ile itaja mọllu náa. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
HWIRL | Níbo ni àwọn ìwé pélébé tí mo fi sí bí yìí wá? | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
HUR4D | Àwọn obìnrin kìí rọ́mọ bí mọ́ tí wọ́n bá ti dé Ipò ìdáààsẹ̀dúró | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
72G2C | Ṣadé pàdánù àwọn òbí-òbí rẹ̀? | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
U4OTB | Ṣé wàá ra ègbà ọrùn náà ní ọ̀sẹ̀ tí ó ń bọ̀ | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
R5QKR | Fáànù àti iná jẹ́ kòṣeémánìí nínú pàlọ́ | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
KSYPO | Wọ́n rí ọmọdékùnrin náà he lójú títì | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
TLGT1 | Gángan ní ìlú tó máa n sọ̀rọ̀ | yoruba | female | 6-17 | phase 1 | |
ZD9SH | ‘Pe bàbá re̩ wa!’, olórí e̩bí pariwo | yoruba | female | 6-17 | phase 1 | |
BVQGV | Àwọn ọmọ yìí ti da aró ìyá aláró nù. | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
JL658 | Ó sin ọ̀rẹ́ rẹ̀ lọ sí ilé ìkọ́ ìmọ̀ ẹ̀rọ ayárabíàṣá. | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
LJP8O | Ìdìbò náà wáyé ní ìbẹ̀rẹ̀ ọdún tó kọjá | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
X1Z8R | Ó ń sọ èdè Italian nítorí pé italy ni ó ti wá. | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
GZ44W | Bàbá rẹ̀ yóò kọ́ ilé àwọn ọmọ aláìníìyá tuntun. | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
8SU86 | njé Ọkọ rẹ ra àpótí òún èló ìkunjú fún ? | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
38MMI | Ẹranko ajẹran ni ìkokò. | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
P73VN | Ọ̀kadà ni ẹ̀gbọ́n mi gùn lọ ibi iṣẹ́ lánàá nítorí sún kẹrẹ fà kẹrẹ ọkọ̀ | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
ZHR4X | Ẹkáalẹ́ ní mo ma kí bàbá lẹ̀yìn wákàtí méjì sí ìsinsìnyín | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
M4J0U | Awọn igbiyanju ojo iwaju yoo ṣe pataki ni piparẹ awọn iwa-ipa irira gẹgẹbi ifipabanilopo ati ifipabanilopo | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
ETBN5 | Mò ń dúró de ọmọ ẹgbẹ́ òṣèlú APC kí a lè jọ lọ ìpàdé | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
PWN0T | Àkókò ìsinmi ni àkókò àlọ́. | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
GQF2Y | Níbo ni ilé yín nínú GRA | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
MXTT9 | Yẹra fún ìwọ́de ìbò ní òní. | yoruba | male | 30-over | phase 2 | |
IF56O | Jide ló ntá gitá yèn | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
OHH5K | Bàbá mi yóò ta gbogbo àwọn ìwé tó wà nínu yàrá tí a má n kó ìwé sí | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
1ZFDK | Àwọn ọkùnrin ìjọ onítẹ̀bọmi máa lọ ṣe ìhìnrere. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
ELC7E | Jọwọ, ṣe iranlọwọ fun mi lati rà bátà tó dàra | yoruba | male | 30-over | phase 2 | |
HPTGN | Ó brown ni àwọ̀. | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
NHXYV | Àwọn ènìyàn sì máa ń gun ọ̀kadà di òní. | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
674MN | Èéfín ni ìwà kò ṣé fi pamọ́. | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
II8KP | Báyọ̀ lọ sí ẹ̀wọ̀n | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
QV6RB | Ìyàwó ló ma ń toọ́jú ìwé ẹ̀rí ìgbéyàwó. | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
HXQUJ | Mi ò pàpà parí ìsìn ní ìjọ Ìràpadà lónìí. | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
MHAQ6 | Àwọn olùkópa ṣe àfihàn ọgbọ́n wọn ní ọ̀nà jíjìn díẹ̀ tí wọ́n ń ṣiṣẹ́ ní ibi eré ìdárayá. | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
WDHXM | Ago mélòó ní ẹ̀ṣọ́ aláàbò náà dé ilé-ẹ̀kọ́ ní àárọ̀ yìí? | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
O0GW8 | Ṣé o ma lọ sí ilé ìjẹun lọ̀túnla? | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
6XYNM | Ǹjẹ́ o ti gba ìwé-ìrìnà rẹ ní ààyè ìṣàkóso ìwé-ìrìnà? | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
H1IP6 | Kolade mú ìdunu wá fún àwọn òbí rẹ̀ | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
S15C9 | Mo máa fẹ́ láti ṣiṣẹ́ ní klíníkì ilé ìwé náà. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
HNSNF | Àwọn ọmọkunrin wọ aṣọ tí wón fí adire ṣe | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
5S4FF | Àwọn èèyàn tó tó igba ló wà níbi ètò ìsìnkù alásinpọ̀ ní Kano | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
LNXDI | Njé o ma gbà waso ? | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
3ZLV0 | Ọjọ́ kẹrìnlá,oṣù Kejì, ni wọ́n ṣẹ̀dá YouTube. | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
MXSBU | Irun fífá jẹ́ ọ̀kan lára iṣé owó. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
9WON7 | Ọ̀pọ̀lọpọ̀ èèyàn ní kò ní lọ sí ọjà nítorí wàhálà tí wọ́n máa dojú kọ | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
NTIVC | Pe gbẹ́nàgbẹ́nà wa sí ibí | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
6BDV3 | Ilé ìwé gíga ti Fáṣítì ní ṣe pẹ̀lú orísìírísìí ilé | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
5TLPT | Ṣo ma pa olè náà ní ìrọ̀lẹ́ yìí? | yoruba | male | 18-29 | phase 1 |
End of preview. Expand in Data Studio
README.md exists but content is empty.
- Downloads last month
- 12