Dataset Viewer
Auto-converted to Parquet Duplicate
audio
audioduration (s)
0.06
32.1
speaker_id
stringlengths
5
5
text
stringlengths
7
177
language
stringclasses
1 value
gender
stringclasses
2 values
age_range
stringclasses
3 values
phase
stringclasses
2 values
KSYPO
Gbogbo ilé-ẹ̀kọ̀ gíga ló ní oríṣi ẹ̀ka ẹ̀kọ́.
yoruba
female
18-29
phase 2
KWHRH
Rárá, mi ò ní tẹ̀lé ọ lọ sí Owerri
yoruba
female
30-over
phase 1
MGWAM
Bẹ́ẹ̀ni, mo rántí láti sá pònmó náà sí inú oòrùn
yoruba
female
18-29
phase 2
P73VN
Ibi ìgbafẹ́ inú ọgbà ni Ṣayọ̀ ń lọ
yoruba
female
30-over
phase 1
HNSNF
Dókítà naa yio we ọmọ tuntun naa léyìn ìbí
yoruba
female
18-29
phase 2
II8KP
Ṣé o lè sọ èdè Lárúbáwá?
yoruba
female
18-29
phase 2
HNSNF
Wọn yóò gbà badminton lórí kootu
yoruba
female
18-29
phase 2
MXTT9
Àwọn ilé-ọtí ìmíì máa ń ní ẹ̀rọ-amóhùnmáwòrán láti wo eré-ìdárayá.
yoruba
male
30-over
phase 2
V3PYU
A lè fi Ayanran se ẹran.
yoruba
male
30-over
phase 1
II8KP
ṣe e n gbè ló si ilé àwọn alarun ọpọlọ?
yoruba
female
18-29
phase 2
EX2CK
Eku po ju ninu yara mi.
yoruba
female
18-29
phase 1
LN4EQ
Ṣé Kúnlé máa dé sí ilé ìgbàlejò?
yoruba
male
18-29
phase 1
0YVR9
Ǹjẹ́́ o nígbàgbọ́ pé ètò ìrìnnà òfurufú yóò túnbọ̀ dára sí lọ́jọ́ iwájú?
yoruba
female
30-over
phase 1
0X1E0
On o mu akero wa ọla.
yoruba
male
18-29
phase 1
IF56O
Éwò ni ki óbìrín fè óbìrín
yoruba
female
18-29
phase 2
2BY6W
Awọn igi jẹ ẹbun lati ọdọ ẹda, ẹwa ati wiwa wọn jẹ iṣura lati ṣe akiyesi.
yoruba
female
18-29
phase 1
U6PC4
Rárá, ọkọ̀ ojú omi kọ́ ni mo fi kó ọjà wá sí Èkó
yoruba
male
30-over
phase 1
GH2S5
Mò ń jẹ ẹja
yoruba
female
18-29
phase 1
VRDR2
Sade fẹràn awọn ẹranko
yoruba
female
18-29
phase 1
Q54MY
Àwọn Adájọ́ máa ń wọ aṣọ aláwọ̀ dúdú àti funfun
yoruba
female
18-29
phase 2
JH83R
Ènìyàn lè kó Ebola nípa jíjẹ ẹran ìgbẹ́ tí kò jiná
yoruba
female
18-29
phase 1
4XT0F
ọ má wẹ omó rè là lè yí.
yoruba
female
18-29
phase 2
GDGSD
Kábínẹ́ẹ̀tì fáìlì náà ti kéré jù.
yoruba
female
18-29
phase 1
29CRO
Ǹjẹ́ o ti wo ìfigagbága ẹ̀sẹ́ kíkàn rí?
yoruba
female
6-17
phase 1
FTF0I
Ní ẹ̀ka ìṣeré ní ilé-ìtajà. Oríṣiríṣi àwọn irúfẹ́ ìṣeré ni wọ́n máa ń ṣàfihàn.
yoruba
female
18-29
phase 1
Z5WFL
Adé ọmọ Yorùbá féràn láti máa jẹ oúnjẹ aláta.
yoruba
male
18-29
phase 1
2T0FS
Ilé ẹjọ́ yóò pọ sí láti fi lè máa parí ìjà
yoruba
female
30-over
phase 1
0IH86
Nigba wo ni olè jíjà náà ṣẹlẹ?
yoruba
male
30-over
phase 1
MAZXB
Mi ò lè gbàgbọ́ pé ọ̀bọ ni ènìyàn tẹ́lẹ̀ rí.
yoruba
male
30-over
phase 1
ZLOOP
Àwọn irúgbìn máa ń gbilẹ̀ wọ́n sì ń gba àwọn ohun èlò ìjẹun.
yoruba
male
18-29
phase 2
OWSIZ
Àgbò méjì kò lè mu omi nínú koto kannáà.
yoruba
male
18-29
phase 1
PLW8F
Délé yóò ṣabẹwo si okò ìlé-ìwé ní ọla
yoruba
male
18-29
phase 1
O0GW8
Aríńkè yọọ̀ jẹ olúṣàkòsó ilẹ̀ itajà ni ọdún tó nbọ
yoruba
male
18-29
phase 2
O0GW8
Nígbàtí mó rí irin-àjò lọ sí United Kingdom ní ọdún tó kọja, mó ríì dájú pé mó jẹ̀ awọn nùdúlù àgọ̀ oriṣíríṣì.
yoruba
male
18-29
phase 2
Q5XTZ
Mo dúró sínú yàrá ẹ̀kọ́ dè ẹ́ .
yoruba
female
30-over
phase 1
HPTGN
Láàbù chemistry kò sí ní sísí.
yoruba
female
18-29
phase 2
4NXF4
Ànàmọ́ ti ń jiná
yoruba
female
18-29
phase 1
Z2Q9X
Sadé fún un ní òògùn kòkòrò fún ojú rẹ̀ tówú.
yoruba
female
30-over
phase 1
Q6KV2
Ìrìn àjò ní orí òkun náà le kún fún òtútù.
yoruba
female
30-over
phase 2
0163F
Ọlá lọ jó salẹńsà rẹ̀
yoruba
male
6-17
phase 1
4NKV8
Ẹnu ní a fí n sọ ààlọ́ fún gbogbo ìran.
yoruba
female
30-over
phase 1
43FB0
Iṣu jẹ oúnjẹ a fún í lókun
yoruba
female
30-over
phase 2
WIT54
O lè rí igi obì ní ìsàlẹ̀ yẹn
yoruba
female
18-29
phase 1
MZTCV
Ṣé kò ní wá gba bátírí rẹ̀ ní?
yoruba
male
18-29
phase 1
HZM4L
Abayomí yóò kọ́ bí a n ṣe sọ èdè pigín
yoruba
female
30-over
phase 2
AU54U
Esita ń yí ata pẹ̀lú ṣíbí ńlá.
yoruba
male
18-29
phase 1
6ADHW
Orò kí òpó mu omi òkú búra yóò dínkù lọ́jọ́ iwájú
yoruba
female
30-over
phase 1
QDMDD
Ó sọ pé "Ti ilé ẹ̀kọ́ ńlá"
yoruba
female
18-29
phase 1
73CNW
Rara, Emi kii yoo fẹ lati ni ologbo bi ohun ọsin ni ọjọ iwaju.
yoruba
female
18-29
phase 1
UN3LQ
Ṣèyí ní àwọn ẹ̀rọ-ìbánisọ̀rọ̀ mẹ́rin-dín-lọ́gbọ̀n-lé-ẹgbẹ̀rún.
yoruba
male
18-29
phase 1
KONPA
Ewé Mọ̀ríngà dára fún dídènà àìsàn ẹ̀jẹ̀ ríru, àìsàn jẹjẹrẹ àti àwọn àìlera ọkàn.
yoruba
female
18-29
phase 1
HPTGN
Ni ibẹrẹ awọn ọdun 2000, Ateronshe Yahoo jẹ aaye lilọ-si fun fifiranṣẹ lẹsẹkẹsẹ.
yoruba
female
18-29
phase 2
K7EWM
Adé yóò ra èédú fún ìyá rẹ̀.
yoruba
female
30-over
phase 1
AJUQK
Pípa ẹja ti bẹ̀rẹ̀ láti bíi ẹgbẹ̀rún ọdún sẹ́yìn
yoruba
female
6-17
phase 1
TL0SY
Ta ni yóò fi àwòrán mi sórí Facebook?
yoruba
male
18-29
phase 1
HPTGN
Bawo ni awọn ilọsiwaju imọ-ẹrọ ṣe le ni ipa lori awọn ohun elo ati awọn eto fun awọn ayẹyẹ igbeyawo ọjọ iwaju, ati awọn iyipada tuntun wo ni wọn le mu wa?
yoruba
female
18-29
phase 2
43FB0
Bẹ́ẹ̀ni, mo máa ń jẹ esunsun.
yoruba
female
30-over
phase 2
FB1SM
Ìṣó náà máa to tan láìpẹ́.
yoruba
male
30-over
phase 1
LCOS2
Ìgbà wo lo ma yan gàrí?
yoruba
male
18-29
phase 1
HNSNF
ìràwọ meji ní Ilé-ìtura yén.
yoruba
female
18-29
phase 2
L6YRG
Germany ni orílẹ̀ tí ó mọ bọ́ọ̀lù gbá jù lọ lágbàáyé.
yoruba
male
18-29
phase 1
J1RGK
Eré burúkú ni awakọ̀ yẹ́n ń sá.
yoruba
male
18-29
phase 1
YTDGU
Ṣe irufẹ núdúsí ní Idomi insitati jẹ?
yoruba
female
30-over
phase 1
XACKJ
Kíni wọ́n fi máa gbé ilẹ̀ náà?
yoruba
female
30-over
phase 1
M9GTI
Yíyan àkàrà èbó jẹ́ àṣà àjèjì tí a gbà ní Nàìjíríà láti ìlú òkèrè
yoruba
female
30-over
phase 1
C36U6
Káfíntà mi lo ṣísù láti fi yọ ìṣó.
yoruba
female
6-17
phase 1
RG8GO
Yinka fún cynthia ní àádọta náírà láti ra bisikí.
yoruba
female
18-29
phase 1
0FXWI
Ṣé asòfin tí dé?
yoruba
female
18-29
phase 1
V6MKF
Bẹ́ẹ̀ni, àwọn òbí rẹ̀ ṣe ìgbéyàwó oníyàwó méjì
yoruba
female
18-29
phase 2
HWIRL
Ibo ni ilé iṣẹ́ asọ̀rọ̀mágbèsì náà wà?
yoruba
male
18-29
phase 1
ZEDKI
Ìdoríkodò àṣà ni yóò jẹ́ bí ìyàwó bá gba ipò ọkọ nínú ilé lọ́jọ́ iwájú
yoruba
female
18-29
phase 1
1KFYQ
Ọpọlọ ń ṣàkóso àwọn iṣẹ́ ara àti àwọn ìlànà ìmọ̀.
yoruba
female
30-over
phase 1
274F3
Wón kó Ọlọ́pàá láti lọ ìbon.
yoruba
female
18-29
phase 1
59INZ
Di ojú rẹ nísinsìnyí!
yoruba
male
18-29
phase 2
MGWAM
Bẹ́ẹ̀ni, mo ka ìròyìn, mo dẹ̀ rí ìròyìn pípẹ́ níbẹ̀
yoruba
female
18-29
phase 2
LA0Y9
Imọ èdè Ṣainíìsì wulo láwàjọ òní
yoruba
female
18-29
phase 2
N7ZN5
Ọmọdẹ́ kìí mọ ẹ̀kọ jẹ kìí o ma ra lọ́wọ́'
yoruba
male
6-17
phase 1
MZLHM
Ọdọọdún ni Olamide máa ń fi àkàrà òyìnbó ṣe ọjọ́ ìbíi rẹ̀.
yoruba
male
18-29
phase 2
W8MQ2
Peeni ti mo lo lana ti sọnu.
yoruba
female
30-over
phase 2
BN1ZC
Àwọn aláìlójútì ń ní ìbálòpọ̀ nínú Odò ìwẹ̀.
yoruba
female
18-29
phase 2
WUSNO
Wọ́n fi ẹ̀sùn ìpànìyàn kan Roland.
yoruba
female
18-29
phase 1
FPLVR
Pẹńtíkọ̀sì máa ń f'èdè fọ̀
yoruba
female
6-17
phase 1
N8JZW
Abọrẹ̀ lo ṣe ètùtù ìyàwó tuntun naa.
yoruba
male
30-over
phase 1
9JXJF
Fà irú erin náà! Ọba pàṣẹ.
yoruba
male
30-over
phase 1
ZHR4X
Mo bọwọ fun awọn aṣa wa.
yoruba
female
18-29
phase 2
SRYA7
Akara jẹ ipanu ti o wọpọ ni Nigeria.
yoruba
female
18-29
phase 2
M1P0A
Rárá à, o lè kó àwọn alárùn ọpọlọ lọ sí ilé àwọn aláìní òbí.
yoruba
male
18-29
phase 1
YT0T2
Ṣé Olùkọ́ wá kọ́ ọ yín lánàá?
yoruba
male
18-29
phase 2
22E62
Lọ gba aṣọ nọ́ọ̀sì mi wá ní ilé ìwòsàn
yoruba
female
6-17
phase 1
BYD73
A lè rí alo nínú àṣà káàkiri àgbáyé.
yoruba
female
18-29
phase 1
UPGFZ
Aláàfin wà ni ààfin.
yoruba
male
18-29
phase 1
HZM4L
Bẹ́ẹ̀ni, o lè yáwó ní ilé ìfọwọ́pamo.
yoruba
female
30-over
phase 2
KY5I7
Bí o ti wù kí ojú ọ̀run funfun tó, sánmò dúdú yóò wà.
yoruba
female
30-over
phase 2
VQCS7
Ó wù mi kì í fojú rí bí wọn ṣe máa ń ṣe ọdún ìbílẹ̀ Oṣogbo.
yoruba
female
18-29
phase 1
ZNHTJ
Gbádébọ̀ túnmọ̀ sí ọmọkùnrin tó gbé adé wọlé
yoruba
male
18-29
phase 1
ELC7E
Titi ló n sé moimoi
yoruba
male
30-over
phase 2
VAO6L
Mo nifẹ jijẹ chinchin
yoruba
male
18-29
phase 2
G2TEL
atégùn kun òórùn adùn òpe òyìnbó ti n jade lati inu ilé ìtajà
yoruba
female
30-over
phase 1
PWGAW
Kò sí enclosure ní ibí.
yoruba
male
18-29
phase 1
3RZ6T
Bólú yóò wá se pásítà yìí ní ìrọ́lẹ́ ọ̀la.
yoruba
female
18-29
phase 1
End of preview. Expand in Data Studio
README.md exists but content is empty.
Downloads last month
19