audio audioduration (s) 0.06 67.2 | speaker_id stringlengths 5 5 | text stringlengths 6 182 | language stringclasses 1
value | gender stringclasses 2
values | age_range stringclasses 3
values | phase stringclasses 2
values |
|---|---|---|---|---|---|---|
YT0T2 | Gbé aṣọ aláró yen wa | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
8F8DL | Àwọn abọrẹ̀ ló máa ń ṣe ètùtù | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
47S2P | Èlò ni Adé fẹ fún ẹ? | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
BPFNB | Irin èsè ó ròrún fún irin àjó àná jijin | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
LM2IX | Oríṣiríṣi àṣọ ni àwọn ọmọ ológun máa ń ní | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
X47RX | Àwọn onímọ̀ sáyẹ́ńsì kan yóò ṣàgbékalẹ̀ àwọn ohun mìíràn láti mú ayé rọrùn. | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
HPTGN | Iya Ige gba ọkọ ní ìmọ̀ràn láti fẹ́ ìyàwó kejì | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
4OOC9 | Fífipámúniṣe wé mọ́ ìwà ìbínú àsọtúnsọ láti pa àwọn ẹlòmíràn lára | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
HPTGN | Idiyele jade yoo wa ni ọna ojurere ti isunmọ awujọ ni ọjọ iwaju | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
9WON7 | Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn mọ́sálásí ló máa n sáábà kún pẹ̀lú àwọn èrò ní àwọn ọjọ́ ẹtì | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
OZCG2 | Òun yóò yońda ohun-ini rẹ silẹ fún ilé ifowopamọ àláwin nítorí kó lé sán àwọn gbèsè rẹ̀ | yoruba | female | 30-over | phase 2 | |
W8MQ2 | Ètò ìgbéyàwó ìbílẹ̀ náà yóò bẹ̀rẹ̀ láìpẹ́ | yoruba | female | 30-over | phase 2 | |
KSYPO | Ọkọ́ ni Ṣadé ń tà. | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
SKABL | Ọkunrin naa sọ pe oun yoo ra maalu nla kan fun igbeyawo ọmọbirin rẹ | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
1BW14 | Jùmọ̀kẹ́ yóò pààrọ̀ ike kànǹkàn rẹ̀. | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
2WJTR | Ẹ̀wà àti búrẹ́dì jẹ́ àjẹpọ̀ óúnjẹ tí ó gbajúmọ̀ jù | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
TMUHG | A máà ń fi ewúro se ọbẹ̀ | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
8Q583 | Ní ilé àwọn alailobi, wọn kì í gbà kí wọ́n yà wọ́n l'àwòrán. | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
2WJTR | Ìgbá náà ti kan | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
ZU5PK | Mudguard dáàbò bo kẹ̀kẹ́ lọ́wọ́ ẹrẹ̀, àti chain náà má ń yí bí īkásè sí ṣe ń yí | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
KY5I7 | Mo pa àlọ́ ìjàpá ati Ẹrin fún àwọn ọmọ mi. | yoruba | female | 30-over | phase 2 | |
6MC70 | Ìyáà mi ni ó máa kọ́kọ́ sọ̀rọ̀. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
7FZHH | Yóò máa tún agbègbè ẹ̀ka ẹ̀kọ́ se láti ọ̀la | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
M8U45 | Bàbá àgbà máa ra ayanran mìíràn ní ọ̀tunla | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
BVQGV | Ǹjẹ́ wọ́n na àwọn ọmọ tó gẹ pọ́ǹkì wá sí ilé-ìwé? | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
EZM5U | Àṣejù ni Títí máa ṣe lọ́la tí ó bá bá ọkùnrin mìíràn sùn nílé ọkọ rẹ̀ | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
BN1ZC | Bàtà tuntun ni Taofiq rà fún ọmọ rẹ. | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
A53P7 | Mo sọ Swedish fún ìgbà àkọ́kọ́ pèlu ìrànlówó Google | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
II8KP | Bọlá tí gbà gbé gbogbo èdè Hausa to gbọ́ | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
P42DO | Àwọn òfin rẹ̀ fìdí múlè nínú ìwé májẹ̀mú tuntun. | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
SX9RB | Ṣé are mọ́tò ìṣeré wà ní ọgbà ìṣeré àdúgbò yín? | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
SRYA7 | Alágbẹ̀dẹ bá mi rọ ilẹ̀kùn onírin lánàá. | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
28VR6 | Adunni yóò pe mi lori foonu ni ọla | yoruba | female | 6-17 | phase 1 | |
PJK68 | Jẹun pẹ̀lú ẹnu rẹ! | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
QF3L3 | Béèni ilé oní yàrá méjì náà ní yàrá méjì, ilé ìgbònsè kan àti ilé ìdáná kan | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
0MK2U | Ṣé inú àwọn ọmọ náà dùn láti wà ní Cairo? | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
HPTGN | Awọn ọrẹ pẹlu awọn eto anfani wa ṣugbọn wọn ko ni ijiroro ni gbangba | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
3D9SN | Awọn ẹjọ ti o kan awọn ẹsun ẹṣẹ ti n gbọ lọwọlọwọ ni agbegbe mejeeji ati awọn sakani iwọ-oorun | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
DRN8W | Awọn aṣa ati aṣa igbeyawo yatọ pupọ ni awọn akoko oriṣiriṣi | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
LNXWF | Àlàntakún kan gùn ẹ́sẹ rẹ sóke | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
HNAPI | Mo ka ìwé alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ ní Àkúrẹ́. | yoruba | female | 6-17 | phase 1 | |
ELC7E | Ìyà mi tó jù gbogbo wa. | yoruba | male | 30-over | phase 2 | |
KERTG | Àná ní bàbá wọ̀ ọkọ̀ òfurufú | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
EQ2IN | Rárá, mi ò rí Amọ̀fin lánàá | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
O0GW8 | Paul sọ́ fún agbẹjọro náà pẹ̀ ọun kò lè gbà ìwé-ẹ̀rí latí ilẹ̀-ẹ̀jọ̀ lánà | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
D1LUP | Jẹ oúnjẹ rẹ! Ẹ̀sọ́ pariwo | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
NEII5 | Bàbá àgbà pa ìtàn ajá àti Ìjàpá fún wa lánàá | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
TKWIS | Ọpẹ́ yóò se ẹ̀wà ní ìrọ́lẹ́. | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
ELC7E | Rárá, Tola ò sí nínú Ilé-ìwẹ̀ | yoruba | male | 30-over | phase 2 | |
8Y12V | Yanju ija pẹlu ọkọ rẹ ni alẹ oni | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
K98X1 | Adeolu máa di ọ̀kan lára àwọn gbajúgbajà onígbàjámọ̀ ni Èkó. | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
Z6OOO | Ní ọ̀la, a máa ṣàwárí ọgbà labalábá náà | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
MV8Y9 | Ipò Kínní ni mo fẹ́ gbé. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
JNHHS | Dúdú ni àwọn táyà ọkọ̀ | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
KY5I7 | ìyá mi pariwo, 'ra sìmẹ́ntí Dangote nìkan' | yoruba | female | 30-over | phase 2 | |
0UMYI | Mo ní pẹ́: irun Dírẹ́dìì rẹ dà? | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
BN1ZC | Ó sọ fun kí ó kúrò lóko | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
M5C3V | Bọlá wá ní bí ọdún Kérésìmesì tí wọn ń ṣe lọ́wọ́. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
NNF2G | Ọmọ márùn-ún ni wọ́n bí sí ilé ìwòsàn àdúgbò mi lánàá | yoruba | female | 6-17 | phase 1 | |
1O7ZA | Wọ́n se ewúro, wọ́n sì fi jẹ ẹ̀bà. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
MGWAM | Wọn ti gbé ọfiisi alákòsó sì búlọ́ọ̀kì tuntun. | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
KY5I7 | A ma ṣe ayẹyẹ ọdún kérésì ní ilé ìwé mi ní òní. | yoruba | female | 30-over | phase 2 | |
O0GW8 | Ma binu ooo ṣugbọn nepa ti ge asopọ ina wa | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
50P0P | Ta ló lọ sí mile 12 láti lọ rata? | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
2WJTR | Rárá o, ìjọ Kẹ́rúbù ló yẹ kí á lọ. | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
II8KP | Ṣé o lè gbá tébú tẹníìsì? | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
GSS7E | Rárá, mi ò tíì ka ìwé ìròyìn náà | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
LET8H | Yóò yọ ọ̀rá núdùsì | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
77Y1D | Mo ní láti ṣàwárí gègé mi. | yoruba | female | 6-17 | phase 1 | |
NJEWX | Ṣe o ṣubu lori ọ̀kadà? | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
INIW3 | Kọjúsọ́kọ jẹ́ àpẹẹrẹ àrà irun tí Yorùbá máa ń ṣe. | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
6JLXU | Igi ni wọ́n fi ń ṣe Ìlarun | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
ZQUY1 | Se Temitope ni oruko omobirin tabi omokunrin? | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
SCZNY | Bàbá àgbà mi fẹ́ràn ìtàn sísọ. | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
DAUVB | Bẹ́ẹ̀ ni, ọkọ ìyàwó fún ìyàwó ní òrùka | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
QBISJ | ràrá mí o mọ nipa Ogun . | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
43FB0 | Ṣé wàá fẹ́ràn láti di ọ̀gágun ọkọ̀ ojú omi? | yoruba | female | 30-over | phase 2 | |
9RSMT | Ó máa rí Yunifásitì aládani ní ìpínlẹ̀ Èkó. | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
UETLS | Ǹjẹ́ wọ́n na àwọn ọmọ tó gẹ pọ́ǹkì wá sí ilé-ìwé? | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
I8Y7I | Ìyè máa ń bu iyì kún ẹni | yoruba | female | 30-over | phase 2 | |
EX2CK | Emi yoo fun ọ ni panla ni ọla. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
Z31O5 | Joonu seleri lati ko okay so egbe ilu e | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
2SCF8 | Kúrò nínú ẹgbẹ́ agbá-bọ́ọ́lù yìí! Olùdarí pàṣẹ. | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
HZM4L | Bẹẹni, Èmí o lọ sí abúlé ifẹhinti | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
II8KP | Bọla fi kọrí sínú ìrẹsì náà. | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
M70L7 | Àwọn ológun jẹ́ ikọ̀ àwọn olùdáàbòbò tí ojúṣe jẹ́ láti dáàbò bo orílé-èdè | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
CTNZ9 | Ọpọlọpọ àwọn ipanu ní a fí fulawa ṣe. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
YT0T2 | Ògùn Àtọ̀gbẹ máa ń ṣisẹ́ nípasẹ̀ jíjẹ́kí Ẹ̀dọ̀ máṣe pèsè ṣúgà àti pé kó má ṣe tú ṣúgà sí ara. | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
RNXAJ | Awọn àjálù mú omijé pẹlu awọn itan ibanujẹ wọn. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
PA33O | Yóò máa bọ̀wọ̀ fún àwọn òbí rẹ̀ láti ìgbà yìí lọ. | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
8T0JL | Ọ̀pọ̀ ọ̀dọ̀ ló sọ oògùn olóró di bárakú nítorí àfarawé | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
3KH48 | Se ironu pupọ le fa aarun ọpọlọ? | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
Q54MY | Kìí ṣé nǹkan ìdùnnú tí oyún bá bọ́ lára obìnrin | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
BN1ZC | o n gbero lati jẹ cashew ti o ba pari ere idaraya | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
WIO8Z | Alternator kuna ati pe o ni lati paarọ rẹ ni orisun omi to kọja | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
FYM3V | Àwọn ẹ̀gbà ọrùn máa ń gbé ìfẹ́ ọrùn ga. | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
3TUIS | Ojerinde yo ra ẹ̀rọ amohunmaworan tuntun lónìí | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
80W5Y | Mo máa ń bẹ̀rù àwọn nọ́ọ̀sì abẹ́lé tó máa ń kó sí búlúù | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
LXBWP | Àwọn kọ́sítọ́mù yóò wo ọjà rẹ ní èbúté ọkọ̀ ojú omi | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
BTKJJ | ògún ẹkú yen kọ pa awọn ẹkú mo | yoruba | female | 30-over | phase 1 |
End of preview. Expand in Data Studio
README.md exists but content is empty.
- Downloads last month
- 23