Dataset Viewer
Auto-converted to Parquet Duplicate
audio
audioduration (s)
0.06
27.6
speaker_id
stringlengths
5
5
text
stringlengths
7
180
language
stringclasses
1 value
gender
stringclasses
2 values
age_range
stringclasses
3 values
phase
stringclasses
2 values
XY5B6
Ológbò máa ń fara nù yàn
yoruba
male
30-over
phase 1
LZYDI
Bẹ́ẹ̀ni, mò ń fi gìta kọrin
yoruba
male
18-29
phase 1
I18DW
Ilẹkun àbáwọlé ńlá máa wà ní ilé kọ̀ọ̀kan ni agbègbè ìgbàlódé.
yoruba
female
18-29
phase 1
OZCG2
gbe awọn ògèdè yẹn sílẹ
yoruba
female
30-over
phase 2
FEEK8
Ta ni yóò jẹ́ ọ̀rẹ́-ìyàwọ mi?
yoruba
female
18-29
phase 1
ZLOOP
Folú rí akawó aláìníwà tí a sọ fún un.
yoruba
male
18-29
phase 2
Q7FW1
Mo ra ọlọ láti máa lọ ẹran náà.
yoruba
female
18-29
phase 2
CCF9T
Àwọn Ìbejì ní wón sọ ní Taye àti Kehinde.
yoruba
female
30-over
phase 1
1KFYQ
ìwé ìròyìn ẹ́ẹ́kọ̀kan wa lori tabili ni yárá Tope.
yoruba
female
30-over
phase 1
W8MQ2
Àwọn ọmọdékùnrin àdúgbò náà máa ṣe ètò alẹ́ àjọ̀dún ní ọjọ́ tó gbẹ̀yìn nínú oṣù yìí.
yoruba
female
30-over
phase 2
MZLHM
Àwọn àwòrán lónàa mílíọ̀nù márùn-úndínlọgọ́rùn ni a máa ń gbe sí orí òpó ìbánidọ́rẹ̀ lójúmọ́.
yoruba
male
18-29
phase 2
A0ZNX
Àwọn ọbí mi sín mi lọ sí pápá ọkọ̀ òfurufú lánàá
yoruba
female
30-over
phase 1
HNSNF
Àwọn ọmọ ẹgbẹ́ òkùnkùn máa mú àwọn ọmọ ẹgbẹ́ tuntun wọlé nípa mimulẹ̀.
yoruba
female
18-29
phase 2
KY5I7
Kọ́ọ̀pù aláwọ̀ funfun yẹn rẹwà gan-an.
yoruba
female
30-over
phase 2
RIA0Z
Ra bọ́ọ̀bù fún mi lọ́la.
yoruba
female
18-29
phase 1
KONPA
Ṣé baba yẹn fi ewé ewé igi-osè wo ẹyin rẹ san?
yoruba
female
18-29
phase 1
71XKC
A béèrè ọ̀nà kii sọnù.
yoruba
female
18-29
phase 1
GPF41
Adájọ́ máa ń rán ọ̀daràn lọ sí ẹ̀wọ̀n.
yoruba
male
30-over
phase 1
7TZW9
Ọ̀pọ̀ ọmọge tí kò fẹ́ ìnira irun ṣíṣe lo má máa gẹrun lọ́jọ́ iwájú
yoruba
male
18-29
phase 2
0IH86
Ìgbà wo ni àbúrò ẹ obìnrin lọ kí ìyá wọn?
yoruba
male
30-over
phase 1
POPB8
Ṣé lóòótọ́ ni ó fún ẹ ní owó lánàá?
yoruba
male
18-29
phase 1
VUV3K
Mo ní mú NIN rẹ wá.
yoruba
male
18-29
phase 1
AMWE8
Má sẹ́ èpè mọ́!
yoruba
male
30-over
phase 1
IF56O
Má bò wá nú òfisi mi
yoruba
female
18-29
phase 2
W5H7H
bàbá yóò so fún wá nipa òrìṣà oya.
yoruba
male
30-over
phase 1
GHD08
Mo máa tan iná tirafikétọ̀ náà nígbà tí mo bá dé bẹ̀
yoruba
male
30-over
phase 1
MZLHM
Kíka ìròyìn lórí eré ìdárayá náà má ń wáyé nínú ìròyìn
yoruba
male
18-29
phase 2
W8MQ2
Wọ́n jí ìwé ìrìnnà náà ní pápákọ̀ òfurufú.
yoruba
female
30-over
phase 2
NAFBF
Ọgá àgbà ilé ẹ̀kọ́ gírámà ní olórí fún ilé ẹ̀kọ́ náà.
yoruba
male
6-17
phase 1
YOQQG
Àjọyọ̀ ọjọ́ ìbí mi máa tó bẹ̀rẹ̀.
yoruba
female
18-29
phase 1
DVK0O
Ọpọlọpọ awakọ̀ ní wọn máa n gbádùn eré sisa ni títí.
yoruba
female
30-over
phase 1
QDMDD
Sẹ́ o wà ní láàbù kẹ́misiri ?
yoruba
female
18-29
phase 1
O54BX
Ta ni ò ń bá jáde lónìí?
yoruba
male
18-29
phase 1
4RPXR
A fún àwọn ọmọ òrukàn ni aṣọ ni ọ̀sẹ̀ tó lọ.
yoruba
female
18-29
phase 1
XIG19
Mo máa gba ṣadínnì táyítọ́sì náà ní ibùdó ọkọ̀
yoruba
male
30-over
phase 1
S40A2
Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ náà jà nínú ilé ìgbé wọn.
yoruba
male
30-over
phase 1
OY9VR
Aṣọ funfun ni gbogbo àwọn ọmọ olóòkú wọ̀ lánàá
yoruba
female
18-29
phase 1
O0RZC
Owó kírípítò kò ní pẹ́ jẹ́ olùdarí ètò ọ̀rọ̀ ajé
yoruba
female
30-over
phase 1
II1GD
Nigbati ewurẹ ba n rin pẹlu Aja, ewurẹ yoo jẹ igbẹ nikẹhin.
yoruba
male
30-over
phase 1
2SCF8
Ọ̀pọ̀ àwọn ọ̀dọ́mọdé ni yóò lọ sí ẹgbẹ́ ọjọ́-orí àwọn ọ̀dọ́ láìpẹ́.
yoruba
female
18-29
phase 2
IUWY6
Akin bèrè fún iyán si.
yoruba
male
18-29
phase 1
KSYPO
Ibẹta ni Ṣadé bí
yoruba
female
18-29
phase 2
HPTGN
Wọ́n rán-an lọ sí ibẹ̀ láti yàrá àwọn olùkọ́.
yoruba
female
18-29
phase 2
SV9JY
Kola ń jẹun lọ́wọ́
yoruba
male
18-29
phase 1
E9ZMS
Àṣe tìẹ ni láti ṣètò isu náà.
yoruba
female
6-17
phase 1
QF1OT
Onisango mọ ògì ẹni tí yóò wà dànù.
yoruba
male
18-29
phase 1
NX2C5
Bawo ni awọn ọna ṣiṣe kika ibile, bii “nnu ego,” ṣe nlo ni awọn iṣe aṣa ode oni?
yoruba
male
18-29
phase 1
MB2KK
O nifẹ lati ló oogun.
yoruba
male
18-29
phase 1
YTOJK
Ọmọdé ni ó máa ń kọ́kọ́ kí àgbàlagbà.
yoruba
female
18-29
phase 1
GC0LB
Àwọn òṣìṣẹ́ ààbò ni wọ́n jẹ́ ojúṣe láti tọ́jú ààbò ilé-ẹ̀kọ́ gíga.
yoruba
male
30-over
phase 1
KY5I7
Bẹ́ẹ̀ni, mo ti rí ẹṣin abilà lọ́pọ̀lọpọ̀ ìgbà.
yoruba
female
30-over
phase 2
HH0CR
Wọ́n jí jáàkì ọkọ̀ mi lọ.
yoruba
male
18-29
phase 2
WIT54
Wo yíì o dékun jìbìtì orí ayélujára
yoruba
female
18-29
phase 1
ZNHTJ
Sátidé lọjọ́ ìgbéyàwó Funbí
yoruba
male
18-29
phase 1
VAO6L
Ibùdó ọkọ̀ ni mo wà
yoruba
male
18-29
phase 2
K0U3K
Bẹ́ẹ̀ni, obìnrin tó gbárùkù ti ilé-ìwé náà fún mi ní owó àpò
yoruba
female
18-29
phase 1
ELC7E
Awòn ópónù nikán ló má n bò órisá
yoruba
male
30-over
phase 2
4XT0F
Ó ń gé ẹ̀fọ́ náà
yoruba
female
18-29
phase 2
X8W40
Àlọ́ àpagbè má ń gùn
yoruba
male
30-over
phase 1
64E8A
Fela Kuti ṣe saxophone pẹlu ifẹ.
yoruba
male
18-29
phase 1
KUOPR
Ilé-èkó sẹkọndiri jẹ ìpele tí ó kàn léyìn ilé-èkó alakobere
yoruba
female
18-29
phase 1
8NDQ2
Ta ni ó pa ẹkùn?
yoruba
male
30-over
phase 1
I18DW
Oríṣìíríṣìí ọkọ̀ ló wà ní ìbùdókọ̀.
yoruba
female
18-29
phase 1
2WJTR
Mo ti pàrọ̀ ìdèdí
yoruba
female
18-29
phase 2
LOISH
Ọkọ ìyá Sule ṣèṣe jáde kúrò ní ewon
yoruba
female
18-29
phase 1
EX7JF
Wọ́n máa péjú ní igbeyawo rẹ̀ ní ìlànà òfin ní òpin ọ̀sẹ̀
yoruba
female
6-17
phase 1
CB5AR
O sọ pe oun yoo nifẹ lati ṣe atunṣe
yoruba
male
18-29
phase 1
CWHE5
Ọlọ́gbọ́n ni í fi ọ̀ràn elòmíràn kọ́gbọ́n
yoruba
male
18-29
phase 1
FZIVE
Ilé iṣẹ́ aṣọ híhun wà ní Idumota
yoruba
female
18-29
phase 1
LA0Y9
Àwọn ọ̀dọ́ máa ń ran àwọn àgbàlagbà lọ́wọ́ ní abúlé
yoruba
female
18-29
phase 2
KY5I7
Mo pàdé Adédoyin ní àná.
yoruba
female
30-over
phase 2
Y4ZAA
Rara, ikoko yii jẹ ọfẹ.
yoruba
male
18-29
phase 1
VTIDE
Rárá, kò ní ṣe ìṣèjọba olówó péréte.
yoruba
female
30-over
phase 1
U8PZ4
Rárá, ẹ̀rẹ̀kẹ́ ni wọ́n ti gbá mi.
yoruba
female
18-29
phase 1
HZM4L
O dẹkùn àwọn adarí alágídí abúlé wa nípa rírọ̀ wọ́n lóyè
yoruba
female
30-over
phase 2
II8KP
Efirin lòdì sí ìdàgbàsókè jẹjẹrẹ nínú ara.
yoruba
female
18-29
phase 2
CSMDP
Wa arábìnrin tó wà ní ipò ìrọbí lọ sí ilé-ìwosàn lọ́wọ́lọ́wọ́ báyìí.
yoruba
female
18-29
phase 2
L9XZN
Àwọn Olóde ilé ìwé ní àyè tiwọn
yoruba
female
18-29
phase 1
HPTGN
Awọn ipo iṣakoso ti ile-iṣẹ atẹjade yoo ṣeese faagun lati pẹlu awọn alamọja titaja oni-nọmba ni ọjọ iwaju
yoruba
female
18-29
phase 2
SAPI0
Àkọni ilẹ̀ Yorùbá ni Mórèmí ń ṣe.
yoruba
female
18-29
phase 1
ZLOOP
Olùdámọ̀ràn máa ń gba àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ní ìmọ̀ràn
yoruba
male
18-29
phase 2
K12YZ
Wọ́n dami sí ẹṣẹ̀ ìyàwó tuntun tí wọ́n fẹ́ kí ó tó wọ ilé ọkọ rẹ̀.
yoruba
male
18-29
phase 1
59INZ
Má mu omi dóngóyárò, obìnrin pariwo!
yoruba
male
18-29
phase 2
UVHS4
Ilé ìfowópamọ́ olókòwò pọ̀ ni Naijiria
yoruba
male
18-29
phase 1
OVFI5
GRA (Agbègbè Ìpamọ́ Ìjọba) túmọ̀ sí àwọn ààyè ìlú tí wọ́n ṣètò dáadáa pẹ̀lú àwọn iṣẹ́ tó dára.
yoruba
female
18-29
phase 2
ZHR4X
Mo ti rí kìnnìún rí ní ilé-ìkẹ́rankopamọ́sí.
yoruba
female
18-29
phase 2
AADVW
Etò ọ̀gbìnmáa túnbọ̀ dara dé ìlò ẹ̀rọ.
yoruba
male
30-over
phase 1
LCVX8
Ẹ́ńjínì ni ọ̀gangan ilé ọkọ̀.
yoruba
female
18-29
phase 1
LR9AV
Àwọn aláṣẹ ló ń darí àwọn ẹgbẹ́ ológun, wọ́n ń ṣe àwọn ìpinnu ìlànà ní pápá.
yoruba
male
18-29
phase 1
MXTT9
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ilé-ìtajà máa ń gba credit cards, debit cards, àti owó.
yoruba
male
30-over
phase 2
43FB0
Ǹjẹ́ wà á se àbẹ̀wọ̀ sí “ olùtọ́sọ́nà ojú-òpó ìpè” ?
yoruba
female
30-over
phase 2
Y0OA6
Ta ló fẹ́ fi ìsebẹ̀ sínú ọbẹ̀?
yoruba
male
18-29
phase 1
FMK0N
Erinmilọ́kun jẹ́ ẹranko ńlá inú omi
yoruba
male
18-29
phase 1
Q6KV2
Wọ́n máa fún aláàrẹ́ẹ̀ ni ògì.
yoruba
female
30-over
phase 2
MWKK9
Ade ṣe irin ajo lo si ilu nla làná.
yoruba
female
18-29
phase 1
OZCG2
Ó sẹ́ ìbáṣepò rẹ̀ pẹ̀lú ẹ̀sìn Confucianism
yoruba
female
30-over
phase 2
FO18W
Èsì kan náà ló máa.
yoruba
female
18-29
phase 1
CDNCT
Mo máa pe àwọn àbúrò mi wá fún oúnjẹ ọ̀sán.
yoruba
female
30-over
phase 1
AIR0P
Bẹ́ẹ̀ni, màá kí ọ káàsán tí mo bá rí ọ.
yoruba
female
30-over
phase 1
SKABL
Béèni, ìyá ìlédìí ọmọ ìkókó náà
yoruba
female
18-29
phase 1
End of preview. Expand in Data Studio
README.md exists but content is empty.
Downloads last month
24