audio audio | speaker_id string | text string | language string | gender string | age_range string | phase string |
|---|---|---|---|---|---|---|
GMA7F | Dókítà náà máa tọ́jú àwọn alaarẹ laipe | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
PMQ6H | Ìtàkùrọ̀sọ máa ń mú ẹ̀mí ìbáṣepọ̀ pẹ́ àti dánmọ́nrán | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
EG4SI | Ikú olórí ilé le fa wàhálà | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
E6K4Q | Ṣé yóò fi oko jíjó láti fi roko? | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
C6TAN | Ilé ìfowópamó̩ Polaris ra ilé ìfowópamó̩ síkáì ní o̩dún márùn-ún sé̩yìn | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
HZM4L | Awọn onimọ-ẹrọ Aeronautical yoo ṣe adaṣe ọpọlọpọ awọn iṣeṣiro | yoruba | female | 30-over | phase 2 | |
QQ19Q | Ọ̀dọ́ ọ̀rẹ́ mi ni mo ti fẹ́ lọ gbọ́ àlọ́ ajẹmọ́ idán. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
MXTT9 | Ohun ìpaná gbọ́dọ̀ wà nínú ọ́fìsì nítorí ìjàmbá iná. | yoruba | male | 30-over | phase 2 | |
CT34Q | Agogo mẹ́fà ní òwúrọ̀ ni ọkọ̀ òfurufú wa yóò balẹ̀ | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
VRDR2 | Síǹkì inú bàlùwẹ̀ Pọ́nmilé ń jò | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
Z6DYR | àbò agbègbè ìyàsọ́tọ̀ ìjọba dáa | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
JY1N2 | Baraka fẹ́ràn iṣẹ́ agbẹ̀bí | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
43FB0 | Tani ó máa jẹ adarí ilé-ẹ̀kọ́ gbogbonìṣe náà lẹ́yìn Ọ̀jọ̀gbọ́n Adeolu? | yoruba | female | 30-over | phase 2 | |
CZCQC | "Yóò mú bàtà náà!" Ìyá mi sọ fún òǹtajà náà. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
BN1ZC | Dáwọ́ ṣíṣe ìtọ́jú ajá yẹn dúró | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
03GAR | Níbi ìnáwó ní ọ̀sẹ̀ tó kọjá, ìyá mi fún ní sẹ̀kẹ̀rẹ̀ | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
UYLLZ | Bola lo gbadura ni mosalasi lana. | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
4DLRT | Sushi náà wà lórí tábìlì oúnjẹ. | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
ADH7T | Sola kò ní tẹ̀lẹ́ ìpinnu àwọn ìgbìmọ̀. | yoruba | female | 6-17 | phase 1 | |
MXTT9 | O nífẹ̀ẹ́ sí Qatiq? | yoruba | male | 30-over | phase 2 | |
UGPLR | Aáwọ̀ inú ilé wà lára èyí tí ó pọ̀ jùlọ ní ilẹ̀ Adúláwọ̀. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
UKMCZ | Majẹmu lopa ọkọ iya walẹ | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
COV1Y | Ekolo jẹ́ kí Ayọ̀ bi silẹ lójijì. | yoruba | female | 6-17 | phase 1 | |
ALHZC | ikú ni yóò ìjìyà fún ìpànìyàn. | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
3KBAT | À ńṣe ètò ìlànà ọba. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
43FB0 | Béèni fíìmù alawada la wò . | yoruba | female | 30-over | phase 2 | |
KY5I7 | Báwo ni o ṣe máa gba sùpàgẹ́tì náà ní ọ̀la | yoruba | female | 30-over | phase 2 | |
Q6KV2 | Ẹ̀fọ́ náà nì yí | yoruba | female | 30-over | phase 2 | |
F0U8E | Mo máa lo ewé ẹ̀jẹ̀ fún àfikún ẹ̀jẹ̀ ara mi. | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
DL6ED | Súnkànmí ránṣẹ́ èébú sí Fẹ́mi lórí Instagram lánàá | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
QV6RB | Òkú ìnáwó ni òkú ìyá àgbà ìjẹta yẹn. | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
ELC7E | Agbégbé idàráyá wó ló má wà lòlá? | yoruba | male | 30-over | phase 2 | |
ELC7E | Titi fè rá áwòn ilàádí tútún lòlá | yoruba | male | 30-over | phase 2 | |
KSYPO | Yọjú sí mi ní Ẹdẹ! | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
G2TEL | Òǹṣẹ̀rẹ́ bìnrin náà féràn eré ìfẹ́. | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
CCO6H | Àjẹ́ náà sọ wípé òun o sọ fún ọkùnrin náà wípé "Kò ní da fún ọ" | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
8HJAE | Má fọwọ́kan àwọn irinṣẹ́ mi | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
HNPBM | Bẹ́ẹ̀ ni, wà á kọrin ní ọjọ́ ìdásílẹ̀ ilé-ẹ̀kọ́ yìí. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
RWUNS | Iyàrá ìgbàlejò ní ibi akọ̀kọ́ tí ènìyàn yóò rí tí yóò sí tí san owó gba iyàrá ní ilé ìgbafẹ́. | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
HFDWN | Ibudọ ọkọ ojú omí sẹ isakoso gbigbẹ́ Lorí omí | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
ELC7E | Awòn ósisë àbó má n wá ni àwòn ilé èkò gigá | yoruba | male | 30-over | phase 2 | |
FQ192 | Ṣé ò ńlọ ilé ìfowópamọ́ ti Ásẹ́ẹ̀sì lọ́la | yoruba | male | 6-17 | phase 1 | |
Q54MY | Nínú bíbélì, ìmùtípara jẹ́ ìṣe ara ẹ̀ṣẹ̀ | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
CHAIN | Ẹ̀sẹ̀ àìmọ̀dí ni wọ́n fi kan Kunle | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
ZZ69K | Ṣe o ń ríi ọlọpa náa? | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
LA0Y9 | Oríṣiríṣi ilé ló wà. | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
O0GW8 | Wọ́n yọ Tọ́lá kúrò nínú ẹgbẹ́ àwọn eégún toripé ó kówó jẹ | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
ZLOOP | Ìtàn ààlọ́ yìí jẹ kí a mọ àwọn akọni tó ti lọ | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
7TZW9 | Ọ̀pọ̀ ọsàn ọlọ́jà ni a ká lórí igi | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
I94DQ | Níbo ni ọ́fìsì ọ̀gá àgbà wà? | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
59INZ | Ó sọ wí pé wọ́n kọ́ àwọn ládìrẹ ní ilè-ìwé | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
OZCG2 | Má fi Mọ́tò rẹ sáré! | yoruba | female | 30-over | phase 2 | |
5013K | Taa ni irọ́ rẹ̀ le jí òkú dìde? | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
RG8GO | Mú ṣíkìn kérésìmesì wá. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
2WJTR | Máa lọ ra jákì ni ọ̀la. | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
28VR6 | Irúfẹ́ ìlù kan ni àgídìgbo. | yoruba | female | 6-17 | phase 1 | |
W8MQ2 | Ẹkùn yẹn ṣi ń robí lọ́wọ́ | yoruba | female | 30-over | phase 2 | |
6JQ3G | Yàrá ìtọ́nisọ́nà àti ìgba'ninímọ̀ràn yóò kó ipa pàtàkì nínú àtìlẹ́yìn àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ní àwọn ọdún tí mbọ̀ | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
327GQ | Ìwà ìrèlè máa ń fúnni ní òmìnira lọ́wọ́ ìgbéraga | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
R5ILL | Ìyàwó kéreré ni ó kàn láti gba inú àgbàlá ní òsè̩ yìí | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
QAJZ7 | Àwọn ẹgbẹ́ àgbẹ̀ ti kóra jọ pọ̀ fún ìpàdé | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
P2Z9X | Ṣe iwọ yóò gba koriko Siperi diẹ fun mi ni ọla? | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
59INZ | Ayíndé yòò jókò ní ààyè ìrọ̀gbọ̀kú àwọn èèyàn pàtàkí jùlọ nítorí pé yòò rá tíkẹ́ẹ̀tì kílásí akọ̀kọ | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
HPTGN | Saheed mọ̀ nípa ìsàré dáadáa. | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
5TLPT | Ṣé o máa fẹ́ mi? | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
ZO98Y | Ama ló sì gboôgan tí àbá ṣetan | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
6NWZ2 | Má a sọ fún àwọn èwe rẹ láti máa pọ́n àgbàlagbà lé. | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
Q7FW1 | Mo fẹ́ràn láti máa yan ènìyàn torí olówó ni mí. | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
43FB0 | Bẹ́ẹ̀ni, ọ̀rẹ́ mi ni lórí òpó ìbánidọ́rẹ̀ fesibúùkù. | yoruba | female | 30-over | phase 2 | |
J0GHA | Mú aṣọ ibùsùn náà wá! | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
6JQ3G | Ìjọba tú gbogbo àwọn ẹlẹ́wọ̀n sile | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
K7C57 | Wọ́n ní ó ti lo àlòjù egboògi olóró. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
LXBWP | Ẹ̀wòn ni wọ́n máa ń kó àwọn ọ̀daràn sí. | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
4XT0F | Tacos jẹ oúnjẹ Mexico kán | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
LG0JN | Ṣé wọn le wo àrùn ètè san? | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
CW7OL | Àwọn ẹgbẹ́ òṣèlú ti ń ṣe ìpàdé. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
CJQFA | Ó jẹ́ olórí ẹ̀ká ẹ̀kọ́ | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
MZLHM | Rárá, dídára ìwé náà kò le dà bíi èyí tí yóò rà | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
JQPJE | Jide ra ẹ̀rọ amúlétutù sí pàlọ́ rẹ̀ | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
N4JQD | Chancellor yoo wa ni ayika ọla. | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
SK7NA | Mo fẹ́ràn ago àti yetí. | yoruba | male | 6-17 | phase 1 | |
7R76Z | Bẹ́ẹ̀ ni, ó nífẹ̀ẹ́ ayẹyẹ Rite | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
FWM6P | Ọjọ́ àìkú àti àbámẹ́ta ní òpin ọsẹ. | yoruba | female | 6-17 | phase 1 | |
7TZW9 | Ṣé Ayinla ń pa àlọ́ àpamọ̀? | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
HH0CR | Èmi àti àwon òré mi se àpèje kékeré kan | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
R3BIH | Gba puff puff meji fun mi | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
MGWAM | Bẹẹni, wọn fún oluranlowo tó wà ní ilé oúnjẹ ní ìwé ìdádúró | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
92JZ4 | Ifeoluwa fún Ifedolapo ni núdùùsì Índòmí díndín. | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
5S4FF | Àwọn ènìyàn ti bẹ̀rẹ̀ sí ní pòǹgbẹ Ìṣèjọba ológun ní àtàrí ìkùnà ìṣèjọba alágbádá. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
ELC7E | Òkúrin lé ni àyá púpò ni ilè ádúláwò | yoruba | male | 30-over | phase 2 | |
SWZ18 | Ṣé wà á kó wọ inú ilé tuntun náà ní ọ̀la? | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
AU54U | Nàìjíríà ní ilẹ̀ gidi. | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
OVFI5 | Lọ gbé ẹ̀rọ amóhungbóná wa. | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
NAFBF | Ọ̀gẹ̀dẹ̀ náà máa so èso púpọ̀ ni ọdún tó ń bọ̀ | yoruba | male | 6-17 | phase 1 | |
L6IL8 | Sọ ma jẹ́ ọ̀dùnkún díndín? | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
MPUZO | Àwọn ẹ̀ka ní kọ́lẹ́ẹ̀jì náà ni Èdè Gẹ̀ẹ́sì, Ìtàn, àti Ìṣègùn. | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
YDVK3 | Ṣé ò ní ṣòkòtò tí o lè yọ̀nda? | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
VUGDK | Máa bẹ̀rẹ̀ láti jẹ alágbàfọ̀ fún ilé ìtura náà láti ọ̀sẹ̀ to ń bọ̀ lọ. | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
MGWAM | Kílódé tí ó fẹ́ wọ ọkọ̀ tí kìí ṣe ọkọ̀ ojú irin | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
XACKJ | Ṣé ayàwòrán ni ẹ́? | yoruba | female | 30-over | phase 1 |
End of preview. Expand in Data Studio
README.md exists but content is empty.
- Downloads last month
- 23