audio audioduration (s) 0.06 24.7 | speaker_id stringlengths 5 5 | text stringlengths 7 177 | language stringclasses 1
value | gender stringclasses 2
values | age_range stringclasses 3
values | phase stringclasses 2
values |
|---|---|---|---|---|---|---|
YT0T2 | Labalábá rẹwà lóòótọ́. | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
CXZOR | Ìyá mi fẹ́ kà nípa grilling. | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
OZCG2 | Má máa bá mi dá àṣàkaṣà mọ bí a bá ń sọ̀rọ̀ | yoruba | female | 30-over | phase 2 | |
EAOSK | Ọgbẹni Okikiola ma tumo owè náà fun mi. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
XB2XZ | Àléfọ tó wà làrà Tunde ti lọ | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
0IH86 | Kíni àwọn irun gígẹ̀ tí ó gbajumo jùlọ láàrin àwọn ọkùnrin ní ayé àtijó? | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
AV00B | Ṣé ẹ̀yin ni ẹ ń dáni lóhùn ní labuu? | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
7OOK5 | Yóò wá pẹlú àwọn kọ́kọ́rọ́ yàrá náà | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
59INZ | Ọ̀já Dei Dei tuntun ni Abuja ni a mọ fun títà ọ̀pọ̀lọ̀pọ̀ awọn èfọ́. | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
CSMDP | A kò gbọdọ̀ fi ọmọ kékeré sílẹ̀ nìkan nínú ilé. | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
MBKD5 | Emá séréré nitóri òjò òlá | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
YT0T2 | Bísí sá eré gbagi gbagi | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
H4DL2 | Wọ́n rà lọ sí ilé-ìwòsàn àwọn alárùn ọpọlọ nítorí lílo òògùn olóró kọ lára. | yoruba | female | 6-17 | phase 1 | |
B10NE | Ṣé o ra ìkó ilẹ̀ ńlá tuntun | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
HZM4L | Ọjà ni ẹ́ ti rí igi àgbọn rà. | yoruba | female | 30-over | phase 2 | |
JNYOA | Àwọn Yorùbá ni ewì àtẹnudẹ́nu. | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
GH2S5 | Irú ń ṣiṣẹ́ fún ojú | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
U8PZ4 | Muiz gbàgbé ẹrù rẹ̀ sínú bóòtù ọkọ̀. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
DDY19 | Jordani nfunni awọn aaye itan bii Petra, fifamọra awọn aririn ajo agbaye | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
4A2VZ | Ọ̀gá àgbà ọkùnrin ni | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
7TZW9 | Mùsùlùmí máa gbàdúrà lóru. | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
5AF8S | Báyọ̀ yóò fẹ́ ìyàwó mẹ́rin lónìí. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
EX2CK | E̩gbè̩fà-ó-lé-mé̩jo̩ ìs̩é̩jú ló wà nínú wákàtí ogún | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
Q6KV2 | Gé gbogbo àwọn òdòdó yẹn lórí. | yoruba | female | 30-over | phase 2 | |
ZO98Y | A ó lọ ọ̀dọ àwọn tí ó ń rán aṣo ọkùnrin. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
FAGZG | Mo n reti lati gbiyanju awọn ami iyasọtọ agbara mimu agbara ni ọjọ iwaju | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
ZHR4X | Wọ́n ní kí n máà bọ̀ ní ọ́físì àwọn olùkọ báyìí! | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
53L1X | Mo máa fọ kọ́tíínì inú yàrá ìgbàlejò. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
OVFI5 | Yóò ra Kẹ́ṣọpù lọ́la | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
KY5I7 | Ọmọdékùnrin náà sáré rádaràda | yoruba | female | 30-over | phase 2 | |
K6BEN | Àgbò iléyá tí bàbá mi rà tóbi gan | yoruba | male | 6-17 | phase 1 | |
VAO6L | Emi yoo tan aṣọ-ikele naa nigbati mo ba ṣetan | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
LRMKP | Ohùn pẹ̀lẹ́ máa ń mú oobi wá láti inú àpò . | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
QFQSP | Olùkọ wa sọ fún wa pé owó ìlú amẹ́ríkà ní iyì ju tiwa lọ | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
2SCF8 | Èṣó yen sí sẹku lọpọlọpọ | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
DHGUM | Mo máa ra bàtà kérésìmesì ní ilé ìtajà Páàmù. | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
B5M3M | Tẹníìsì ni màá máa gbá nísìnyín. | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
7OUVV | Ṣé ojú mi pupa? | yoruba | female | 6-17 | phase 1 | |
8F8DL | Òótọ́ ni pé ohun à ń wá lọ Ṣókótó wà ní ìsàlẹ̀ ṣòkòtò. | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
Q6KV2 | Wọ́n fún wa ní óunjẹ nínú ọkò òfurufú | yoruba | female | 30-over | phase 2 | |
OVFI5 | Ìkórè máa ń mú kí ohun ọ̀gbìn dàgbà | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
PWN0T | Ère méta wà ní ìpínlẹ̀ Èkó | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
KY5I7 | Mi ò fẹ́ràn láti máa fi igi ìfọyín mi lọ́. | yoruba | female | 30-over | phase 2 | |
ZHR4X | Èló ni ẹ̀ ń ta òkòókan àwọn adìẹ yìí? | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
F354Y | Agba ọmọ jọ́ lọmọ ń mojú. | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
ZN0W8 | Mo nílò àáké. | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
QWZAL | Mo lọ rí bàbá ọkọ mi nínú ilé ẹbí. | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
KSYPO | Dídi ọwọ́ àwọn ọmọ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ mú ṣe kókó. | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
5ESID | Oṣù Èrèlè ni oṣù Kejì ọdún. | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
G1IQ9 | Ó wà nínú cyber bullying. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
A5LD3 | Ó kò gbọ́dọ̀ wọ aṣọ sójà mọ láyé. | yoruba | female | 6-17 | phase 1 | |
7020G | Bàálù máa ń fò ní òkè | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
HH0CR | Orúkọ bàbáà mi ni Adébáyọ̀ | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
K6BEN | Bàbá mi tẹ ọkùn náà pa ní òwúrò yìí | yoruba | male | 6-17 | phase 1 | |
V8VTJ | Máa di irun rẹ ni gbogbo igba! | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
I94DQ | Àwọn olùkọ́ máa ń dúró sí yàrá fún àwọn olùkọ́ nígbà tí wọn kò bá sí nínú yàrá ìkàwé. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
D7N9Z | Yorùbá rí wọn gẹ́gẹ́ bí i iyọ̀ ayé. | yoruba | female | 6-17 | phase 1 | |
MHAQ6 | Lọ́la, Yemi yóò gbé ìgbẹ́kẹ̀lé ró nípa mímú ìlérí rẹ̀ ṣẹ fún àwọn ọ̀rẹ́ rẹ̀. | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
P10VD | Ẹgbẹ́ tíátà Fẹ́mi Adégbilé máa gbilẹ̀ dáadáa lọ́jọ́ iwájú | yoruba | female | 6-17 | phase 1 | |
06JTV | Mo kórira díríí jin | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
SV9JY | Wọ́n ti sún ọjọ́ ikú Kọ́lá si ọ̀lá | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
CIUZC | Àkúdayà ni obìnrin náà | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
12818 | a lè fi eja inu agolo sardine tabi alara je burẹdi | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
IF56O | Toyin fè ló àdá yèn lòtúnlá | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
5013K | Gómìnà wa ń fi ìwà ọmọlúàbí ara rẹ̀ tún ìlú ṣe | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
CSMDP | Ọ̀gẹ̀dẹ̀ yìí kò tí ì gbò ó. | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
V0JI2 | Paapaa ni ọjọ iwaju awọn ara ilu India yoo tun ṣe adaṣe eto idile apapọ kan | yoruba | female | 6-17 | phase 1 | |
G1ERL | Arábìnrin arúgbó náà n'ifẹ sí ilé kékeré sí ilé ìtura nlá | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
IU7RH | Dandan ni ki awon ológun ni àbòrí. | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
2SCF8 | Bàbá mi fẹ́ fún ìyá mi ní ẹ̀bùn ọkọ̀ lọ́jọ́ ìbí wọn. | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
XRJ7H | Yínká fún Cynthia ní àádọ́ta náírà fún bisikíìtì. | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
MB6VH | Bẹ́ẹ̀ni, po ọ̀dà náà pọ̀ | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
JT49F | Nibo ni iwọ yóò tọju ibon rẹ? | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
MXTT9 | Yewande di "Iyalode" nípasẹ̀ ayẹyẹ àdéhùn ìtàn, tí ó ṣe àmì ipa olórí rẹ̀. | yoruba | male | 30-over | phase 2 | |
Q54MY | Ohun èlò tí a lè rí ní ilé oúnjẹ ni abọ́, ṣíbí,àga, tábìlì,abbl. | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
HPTGN | Itọju aboyun jẹ abala pataki ti ilera oyun, ni idaniloju oyun ilera | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
OY31B | Àwọn babaláwo máa ń bá àwọn ènìyàn ṣe ògùn owó. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
ZLOOP | Oríṣiríṣi àwọn ẹ̀wọ̀n ní àwọn ìpele tí ó yàtọ̀ | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
GPF41 | Jídé máa ya àwọn ohun àlùmọ́ọ́nì. | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
QMC1R | Ògá Sójà àti Kópírà yóò pàṣẹ fún àwọn ọmọ ogun pẹ̀lú ọ̀nà ìkọ́ṣẹ́ mọṣẹ́ | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
NSVL6 | Dèjì yóò kópa nínú eré orí ìtàgé kan nínú tíátà Wo̩lé S̩óyínká tó wà ní ilé-ẹ̀kọ́ yunifásítì Ìbàdàn ní ò̩la | yoruba | female | 6-17 | phase 1 | |
OQZCC | Búrẹ́dì ò kí ń ṣe ìpanu | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
NANQZ | Bẹ́ẹ̀ni, àwọn gbẹ́nàgbẹnà náà ti bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ wọn. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
KSYPO | Àwọn alágbẹ̀dẹ ló ń rọ ọkọ́ | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
ELC7E | A ó sọ̀rọ̀ ni pápá abúlé ní ọ̀la | yoruba | male | 30-over | phase 2 | |
GCMCG | Fèrèsé àlùmákò máa ń bu ẹwà kún ilé | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
YT0T2 | Ewúro máa dínkù àrùn a ìjẹun gbìn. | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
P42DO | Orúkọ rè ńjé Fáloba nítorí pé Ifá ni wón ń sìn nínú ẹbí i rè | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
P73VN | Wọ́n mú aṣọ ẹgbẹ́jọdá fún ayẹyẹ ìgbadé ọba tuntun ti ìlú ìsẹ́yìn | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
L95SJ | Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àǹfààní ni ayélujára ń pèsè fún àwọn ènìyàn | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
IG3S1 | Ọjà tí ó tà jùlọ ni sọ́ọ̀bù rẹ̀ ni ohun mímu ẹlẹ́rìndòdò | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
CSMDP | Ó sòwọ́n kí káfíntà ó máa ní hámà. | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
M5C3V | Ìyá Bọlá ń mú yúgọ́ọ́tì lọ́wọ́ | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
ZLOOP | Tẹ̀lé mi lo sí mósálásí | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
Q6KV2 | Gbogbo ọjọ́ abameta ni a máa ń mu ewé elegede mọ maltina. | yoruba | female | 30-over | phase 2 | |
GF0ZT | Ní ile Yorùbá, wọn máa ń wo ohun tí ọmọ máa dà lọ́jọ́ ọlá nígbà tí wọ́n bá ṣẹ̀ṣẹ̀ bi. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
L88Q7 | Ẹni tó máa n purọ́ ni wọ́n pè ní òpùrọ́ | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
140SC | Adarí ilé-ìwé na àwọn tó pẹ́de. | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
HL8TT | Mò ń yan ẹran náà kí ó má balè bàjẹ́. | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
TI10X | Bẹ́ẹ̀ ni, ó rí ìwé ìtàn tí ó fẹ́. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 |
End of preview. Expand in Data Studio
README.md exists but content is empty.
- Downloads last month
- 15