audio
audioduration (s) 0.06
20
| speaker_id
stringlengths 5
5
| text
stringlengths 8
183
| language
stringclasses 1
value | gender
stringclasses 2
values | age_range
stringclasses 3
values | phase
stringclasses 2
values |
|---|---|---|---|---|---|---|
MHAQ6
|
Lọ sí ìṣelọ́pọ̀ tíátà ìbílẹ̀ láti ní ìrírí òṣèré àti ìtàn.
|
yoruba
|
male
|
30-over
|
phase 1
|
|
QBISJ
|
Rárá, mi ò fẹ́ jẹ ṣíńṣiǹ
|
yoruba
|
male
|
30-over
|
phase 1
|
|
GNNQV
|
Francis tí bẹ̀rẹ̀ Ìdánilẹ́kọ̀ọ́ èdè Íbò pẹ̀lú mi lánàá
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 1
|
|
XVPXV
|
Rárá, mi ò lọ sí ilé ẹ̀kọ́ ni ọ̀la.
|
yoruba
|
female
|
30-over
|
phase 1
|
|
L88Q7
|
Ẹbí olóbìnrin púpọ̀ jí èyí tí ọkùnrin kan bá fẹ́ ju obìnrin kan lọ.
|
yoruba
|
male
|
30-over
|
phase 1
|
|
ZHR4X
|
Mo máa mú jígí ọkọ̀ tuntun náà wá fúnra mi
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 2
|
|
ZHR4X
|
Mo máa se núdùsù láàárọ̀ ọ̀la.
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 2
|
|
YT0T2
|
The government will build houses for the workers
|
yoruba
|
male
|
18-29
|
phase 2
|
|
5L5RA
|
Àwọn ẹgbẹ́ máa ń ṣe ìdìbò láàárín ara wọn
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 1
|
|
YKRRX
|
Awọn ọbẹ abinibi máà ń wa ni awọn ayẹyẹ
|
yoruba
|
female
|
30-over
|
phase 1
|
|
12818
|
A lè fi sardinni jẹ búrẹ́dì
|
yoruba
|
male
|
18-29
|
phase 1
|
|
59INZ
|
Akíkanjú ọkùnrin ni ọkùnrin ta rí lọ́jà lánàá
|
yoruba
|
male
|
18-29
|
phase 2
|
|
VVKH2
|
paramilitary agbari yẹ ki o ni ilọsiwaju ni isẹ ni akoko ti mbọ.
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 1
|
|
ECGRM
|
Mo n yan ipele aladun miiran ti awọn kuki chirún chocolate.
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 1
|
|
3W24E
|
Má ṣe àgbèrè.
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 1
|
|
ZLOOP
|
Ṣé o ní kámẹ́rà?
|
yoruba
|
male
|
18-29
|
phase 2
|
|
GH2S5
|
Òróró wà fún jíjẹ
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 1
|
|
LGUC3
|
Adigun gbe awon omo re lo si sinima
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 1
|
|
HPTGN
|
Awọn itura ere idaraya ti ọjọ iwaju yoo ṣaajo si awọn aṣa ere idaraya ti n yọju ati awọn iṣẹ ere idaraya lọpọlọpọ
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 2
|
|
2QH6K
|
Ọ̀pọ̀ ìjọ ló ní gángan.
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 1
|
|
L88Q7
|
Ọkò òfurufú kìí balẹ̀ sórí koríko.
|
yoruba
|
male
|
30-over
|
phase 1
|
|
L88Q7
|
Arákùnrin-bàbá ni ẹ̀gbọ́n tàbí àbúrò ọkùnrin bàbá ẹni ń ṣe.
|
yoruba
|
female
|
30-over
|
phase 1
|
|
MZLHM
|
Ìsomọ́ọ̀dí Pampers di ṣíṣẹ̀dá sílẹ̀ ní 1961.
|
yoruba
|
male
|
18-29
|
phase 2
|
|
B10NE
|
Mo lo búròsì ọ̀dà kùn ara ògiri
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 1
|
|
AOT3M
|
Ṣé o ti ra bọ́tà tí ìwọ yóò fi ṣe àkàrà òyìnbó?
|
yoruba
|
male
|
18-29
|
phase 1
|
|
43FB0
|
Ṣé àwọn akẹ́kọ̀ọ́ náà yóò tètè dé ilé-ìwé ní àárọ̀ ọ̀la?
|
yoruba
|
female
|
30-over
|
phase 2
|
|
FHUTC
|
Àwọn gbajugbaja náà fẹ dé
|
yoruba
|
female
|
6-17
|
phase 1
|
|
W8MQ2
|
Bàbá náà ṣe ara rẹ̀ lẹ́sẹ̀ lánàá
|
yoruba
|
female
|
30-over
|
phase 2
|
|
4XT0F
|
Ọ̀pọ̀ ènìyàn ló ń gbé nínú gẹ́tò.
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 2
|
|
BN1ZC
|
Kó gbogbo àwọn ìwé náà wọlé tí wọ́n bá ti tẹ̀wọ́n tán
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 2
|
|
2SCF8
|
Mọ́remí jẹ́ òrìṣà to jẹ́ obìnrin
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 2
|
|
OVFI5
|
Ṣé o ti rí kẹ̀kẹ́ Márúwá rí?
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 2
|
|
OZCG2
|
Jíjà fún ètó rẹ̀ ló dára ju láti se fún ènìyãn
|
yoruba
|
female
|
30-over
|
phase 2
|
|
Z6DYR
|
Sanni Abacha ti fi ìgbà kan jẹ́ olórí ológun.
|
yoruba
|
female
|
30-over
|
phase 1
|
|
3F4VN
|
Pelu ipa ọna-ọna, a tun jẹri ijabọ ni ọsẹ to kọja.
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 1
|
|
43FB0
|
Ta ni yóò mú kaṣú wá fún mi?
|
yoruba
|
female
|
30-over
|
phase 2
|
|
ZAZDI
|
Báyọ̀ sọ pé abúlé òun ń ṣe ìjọba anìkannpàṣẹ
|
yoruba
|
female
|
6-17
|
phase 1
|
|
E55SZ
|
Awọn ile-iwe ni igba atijọ ko ni awọn
|
yoruba
|
male
|
30-over
|
phase 1
|
|
AGDH6
|
Bẹ́ẹ̀ni, èrò yóò pé kátó lọ.
|
yoruba
|
male
|
30-over
|
phase 1
|
|
SRYA7
|
Akọ̀we ni ẹni tó ń rí sí iṣẹ́ ètò ìṣúná kọ́lẹ̀jì tàbí fáfitì.
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 2
|
|
OY31B
|
Èṣó tí a ní tó fún wa.
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 1
|
|
AA0QX
|
Máyọ̀wà ló gbé ọkọ̀ síbẹ̀.
|
yoruba
|
male
|
30-over
|
phase 1
|
|
72TR9
|
alakoso yíò ṣàkóso ile ifowopamọ kekere
|
yoruba
|
male
|
18-29
|
phase 1
|
|
ELC7E
|
Ègbè àjè jè ègbè áwòn óbirin
|
yoruba
|
male
|
30-over
|
phase 2
|
|
MZLHM
|
Paul féràn burẹdi rè pẹlú Jam.
|
yoruba
|
male
|
18-29
|
phase 2
|
|
D1A30
|
Bẹẹni, igbese sise mọ́í-mọ́í yàtọ̀ sí àkàrà.
|
yoruba
|
male
|
30-over
|
phase 1
|
|
HPTGN
|
Bàbá àgbà ló ni oògùn ojú náà
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 2
|
|
HH0CR
|
A máa ń fi ohun ìkó ewé pa ilẹ̀ mọ́
|
yoruba
|
male
|
18-29
|
phase 2
|
|
N03J6
|
Wọ́n fipá mú àwọn ọ̀dọ́mọkùnrin náà lálẹ́ àná.
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 1
|
|
AJUQK
|
First bank pe ogorun odun ni odun die seyin
|
yoruba
|
female
|
6-17
|
phase 1
|
|
V1F3V
|
Alakẹ máa di irun ìhun fún ọmọ rẹ ni ọ̀la
|
yoruba
|
male
|
18-29
|
phase 1
|
|
KCAHL
|
Ṣé ẹfọn pọ ni ìjeta?
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 1
|
|
TKWIS
|
ìfipá-bá-ni-lò-pò túnmọ̀ sí wípé wón fi típà típà ba ẹni Kejì ni àjọ ṣẹpọ.
|
yoruba
|
male
|
18-29
|
phase 1
|
|
D87Y7
|
Orúkọ ọmọ ni ìjanu ọmọ.
|
yoruba
|
male
|
18-29
|
phase 1
|
|
2SCF8
|
Ìyá mi ti tajà rí lọ́jà Òyìngbò.
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 2
|
|
R1SHI
|
Ìyá Bọ́lá máa ń sun ẹran wọn.
|
yoruba
|
female
|
30-over
|
phase 1
|
|
1EORU
|
Wàá tún ọkọ̀ yẹn ṣe!
|
yoruba
|
female
|
30-over
|
phase 1
|
|
MTYGU
|
Ìtọ́tẹ̀ pupa ni wàá lò fún Tolú.
|
yoruba
|
female
|
6-17
|
phase 1
|
|
9MWSV
|
Èmi ń ṣe tábìlì titun fún ara mi.
|
yoruba
|
female
|
30-over
|
phase 1
|
|
KSYPO
|
Wọn ti gbé Kọ́lá lọ sí ilé ìtọ́jú ọpọlọ ní Abẹ́òkúta
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 2
|
|
LVJKM
|
Àdàpọ̀ Sìmẹ́ntìì,Omi ati iyẹ̀pẹ̀ ni o di Kọnkéré
|
yoruba
|
male
|
30-over
|
phase 1
|
|
3ZVRE
|
Ìyíṣòó lo má fi yọ èṣó.
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 1
|
|
2JZTK
|
Ní àtijọ́, wọ́n bọ̀wọ̀ fún ọba gan-an .
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 1
|
|
9ZDVW
|
Níkẹ̀ yan báǹkì ìfowópamọ́ ìsanwó.
|
yoruba
|
male
|
18-29
|
phase 1
|
|
L1GCM
|
ẹ̀sán -dín- ní- ẹgbẹ́ẹ́ẹdógún ni bureau de change ni orílè-èdè Nàìjíríà.
|
yoruba
|
male
|
30-over
|
phase 1
|
|
2SCF8
|
Báǹkì ayánilówókọ́lé ni bàbá ọ̀rẹ́ mi ti ṣiṣẹ́ kó tó kú.
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 2
|
|
AGXXX
|
A máa ń to ọjà ní ìpele bí wọ́n ṣe rí.
|
yoruba
|
female
|
6-17
|
phase 1
|
|
NNEZM
|
Ṣé ìdílé tí obìnrin tí ń pàṣe ni o ti wá?
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 1
|
|
E55SZ
|
Awọn oju iṣẹlẹ jẹ àrà awọn fíìmù.
|
yoruba
|
male
|
30-over
|
phase 1
|
|
LRMKP
|
àrà júù kán yíò wá lóni
|
yoruba
|
male
|
30-over
|
phase 1
|
|
L2SYI
|
Ọsẹ ti n bọ ni opun-dé.
|
yoruba
|
female
|
30-over
|
phase 1
|
|
RXZ9I
|
Mo máa mú abọ́ núdùsì náà ní ọ̀la
|
yoruba
|
female
|
30-over
|
phase 1
|
|
WSYC1
|
Àwọn àṣá mà n pà awọn òròmọdìẹ
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 1
|
|
HH0CR
|
Àfarawé máa túbọ̀ di wàhálà ńlá síi ní ọjọ́ iwájú.
|
yoruba
|
male
|
18-29
|
phase 2
|
|
LA0Y9
|
Olusho Ẹnubodè yoo kii itara ati ṣetọju aabo lori agbegbe naa
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 2
|
|
OZCG2
|
Má darapọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ òṣèlú kankan
|
yoruba
|
female
|
30-over
|
phase 2
|
|
4DFWI
|
Bayo nkò ilé rè
|
yoruba
|
female
|
30-over
|
phase 1
|
|
V6MKF
|
Arábìnrin náà ra ọṣẹ ìfọrun
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 2
|
|
VUGDK
|
Mo máa fi àtẹ̀jíṣẹ́ ránṣẹ́ sí ẹ lóri Facebook.
|
yoruba
|
female
|
30-over
|
phase 1
|
|
NIVJV
|
Wọn gbé aláìsàn náà lọ sílé ìwòsàn.
|
yoruba
|
female
|
30-over
|
phase 1
|
|
GTIZ0
|
Bàbá mi jẹ iyán náà?
|
yoruba
|
female
|
30-over
|
phase 1
|
|
GVGH3
|
Awọn ile ayagbe yoo ṣe atunṣe fun awọn ohun elo to dara julọ ni igba ikawe atẹle
|
yoruba
|
male
|
18-29
|
phase 1
|
|
9ZDVW
|
ìjọba Nàìjíríà ò lè ṣe ìrànlọ́wọ́ kankan fún ará ìlú.
|
yoruba
|
male
|
18-29
|
phase 1
|
|
M5C3V
|
Bọlá máa lọ sí ọdún ifá ni ọ̀la.
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 1
|
|
P73VN
|
Àbíkẹ́ mu abẹ̀bẹ̀ wọ yàrá ìdánilẹ́kọ̀ọ́ ti dọkita Oyè.
|
yoruba
|
female
|
30-over
|
phase 1
|
|
COA80
|
Tọ́lá fẹ́ ra fìlà
|
yoruba
|
male
|
30-over
|
phase 1
|
|
LA0Y9
|
Olùkọ́ a fún àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ní iṣẹ́ àmúrelé á sì máàkì rẹ̀.
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 2
|
|
0OVNP
|
Ọ̀la ni ìsomolórúko náà
|
yoruba
|
female
|
30-over
|
phase 1
|
|
MB2KK
|
Oń wá aṣojú lóge.
|
yoruba
|
male
|
18-29
|
phase 1
|
|
QV6RB
|
Awọn ọmọle loorekoore ọja lati ra simenti, kọnkiti, awọn ọpa, ati bẹbẹ lọ
|
yoruba
|
male
|
18-29
|
phase 1
|
|
DVEZH
|
Ẹ̀rọ kọ̀m̀pútà mẹ́rin ni ó wà nínu yàrá kọ̀m̀pútà náà.
|
yoruba
|
male
|
30-over
|
phase 1
|
|
0EA9E
|
Béèni àwọn òbí ré yóò já nítorí àìbìkítà.
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 1
|
|
KSYPO
|
Ìṣọ̀lá fọ́ irinṣẹ́ àwòrán Tọ́lá.
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 2
|
|
GF0ZT
|
Ní àtijọ́, kò wọ́pọ̀ fún àwọn akẹ́kọ̀ọ́ láti lọ sí ilé ìwé lẹ́yìn ọdún mẹ́rìnlá
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 1
|
|
BQYLC
|
A rí àwọn koríko díè lórí àpáta.
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 1
|
|
59INZ
|
Báyọ̀ sọ pé abúlé òun ń ṣe ìjọba anìkannpàṣẹ
|
yoruba
|
male
|
18-29
|
phase 2
|
|
ZHR4X
|
Mò ń sin ẹṣin
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 2
|
|
05HN6
|
Tà lo kùn ilẹ̀ rẹ̀?
|
yoruba
|
male
|
18-29
|
phase 1
|
|
SBLJM
|
Wọ́n máa ń pàtẹ ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹ̀fọ́, ata àti tòmátì ní àràárọ̀ ní Ẹlẹ́yẹlé.
|
yoruba
|
male
|
18-29
|
phase 1
|
|
KSYPO
|
Àkànmú wọ ṣòkòtò àti ẹsikí
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 2
|
End of preview. Expand
in Data Studio
README.md exists but content is empty.
- Downloads last month
- 2