audio audio | speaker_id string | text string | language string | gender string | age_range string | phase string |
|---|---|---|---|---|---|---|
S47FP | Àwọn ọ̀dọ́ rìn lọ ààfin ọba lónìí? | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
ELC7E | Funbí mú àádòje gíláàsì wá lọ́jọ́ tó kọjá | yoruba | male | 30-over | phase 2 | |
OVFI5 | Bàbá bàbá rẹ̀ gbin igi púpò sínú igbó | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
4XT0F | Ìtàn ẹ̀sìn sọ̀rọ̀ nípa àwọn ǹkan nínu ẹ̀sìn kan tàbí òmíràn | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
O0GW8 | Igi àgbálùmọ̀ ta rí ní ilé Kíkẹ́ lánàá ò léso | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
OVFI5 | Lọ sọ̀rọ̀ nípa àṣà ìkíni ilẹ̀ Yorùbá! | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
MZLHM | Rárá, òpò obínrin kò mo pàtàkì ìtójú oyún nígba àtijó? | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
9WON7 | Àìsàn òwúrọ̀ jẹ́ àmì ìlóyún tí o wópò, asì ma se ìdá ogórín àwon obìrin | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
ZLOOP | Wọ́n gba èdè Gẹ̀ẹ́sì gẹ́gẹ́ bí èdè òṣìṣẹ́ Nàìjíríà ní sẹ́ńtúrì ogún. | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
7SK26 | Èmi àti àwọn ọ̀rẹ́ lọ ki ẹbí ẹni tó kú. | yoruba | female | 6-17 | phase 1 | |
SCSDY | Àwọn pírífẹ̀tì ilé-ìwé náà kó ipa tó ṣe pàtàkì nípa kíkó ara ẹni ní ìjánu | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
YT0T2 | Àwọn ọmọdé ayé òde òní féràn eré orí fóònù. | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
MXTT9 | Fáànù ara ògiri máa ń wà lára ògiri, ó sì máa ń fẹ́ afẹ́fẹ́ kárí ilé. | yoruba | male | 30-over | phase 2 | |
JO8XJ | Àwọn sítai irun ìgbàlódé tuntun síí máa jáde lọ́jọ́ iwájú | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
XPYBH | ṣe o ní òye àlọ́ àpamọ̀ rẹ? | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
JVDL9 | Bọ̀dá mi máa dé láti òkè-òkun ní ọdún tó ń bọ̀ | yoruba | male | 6-17 | phase 1 | |
MXTT9 | A máa ń fi ẹsẹ̀ rìn. | yoruba | male | 30-over | phase 2 | |
IF56O | Òkò ójú ómi lá wó lò si Lèki nijètá | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
KYBY1 | Mo ní kí Joel ṣọ eré fọ́ọ̀kí tí ìyá ìyá rẹ̀ ṣọ fún -un fún ẹ | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
XOYTO | Ní atijọ́, àwon bàbá ni a ma n ri gẹgẹ bi olórí ẹbí, won ma n pèsè fun ilé won | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
X2ROS | O ti wa ni rin nipa reluwe! baba re wipe | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
V6MKF | Arábìnrin Teni sọ́ pẹ̀ ọ̀un ń yoo lọ sí ilẹ̀ ni ọ̀lá lati sọ́ fún ẹbí wọn nípà òlè rẹ. | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
OYLDH | a o wà ninú ilé lọla nítorí ajodùn Orò | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
CGXXR | Ò ń sùn nígbà tí ó ṣẹlẹ̀ | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
2NA7U | Táyọ̀ ó ṣí ilé oúnjẹ búkà lọ́dún tó ń bọ̀ | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
20BEB | Béèni o tí dì osi ọba. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
ZLOOP | Àwon bàbá làti mo gẹ́gẹ́ bi olórí ebi, nìsnsìnyí won ti n se àjopín ojúse won bayi | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
IF56O | Mó ti tán kòmpútá òfìsí silé | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
BN1ZC | Ẹ̀ṣọ́ aṣọ́bodè ní kẹ́ yin èrò ọkọ̀ Òfurufú náà dúró! | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
HZM4L | Adekunle tọ́jú ìwé ìròyìn ṣíbí | yoruba | female | 30-over | phase 2 | |
AHT53 | Ọ̀gá Babatunde pàṣẹ fún àwọn òṣìṣẹ́ rẹ. | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
DQIRE | Odung jẹ irú awòrán ara ti a ló fún awọn iṣẹlẹ bíi ìgbéyàwó, ìbímọ, ọ̀jọ-ọ̀ri, àti ìkù nípasẹ̀ awọn ènìyàn Ìbibio. | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
GBTGX | Ilé-ìwe gíga politẹ́kínìkì ní Ṣadé lọ. | yoruba | female | 6-17 | phase 1 | |
WN9Q2 | Ìyá rẹ̀ máa n gbé oúnje wá fún wa | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
8UOIO | Ọjọ́ kan ni ìgbéyàwó náà. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
NZ4Y3 | Wọ́n de ọwọ́ mi ní okùn. | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
QLGXT | Igi ni a fi ń kan ilé | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
MZLHM | Ìjọba tí ó wà ní ọwọ́ àwọn ọlọ́rọ̀ àti bọ̀rọ̀kìní ni òlígákì. | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
YTDGU | Ṣúgà dúdú wà lára èròjà ìbílẹ̀ fún ẹ̀wà yiyan | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
HZM4L | Lẹ́yìn ọ̀pọ̀ wákàtí tí wọ́n ti ń fọ̀rọ̀ wá lẹ́nu wò, Ẹlẹ́rìí náà sọ̀ kalẹ̀ láti orí ìdúró náà. | yoruba | female | 30-over | phase 2 | |
KY5I7 | Javeline ni mo mọ̀ ọ́ jù. | yoruba | female | 30-over | phase 2 | |
5OB21 | Igigirísẹ̀ ẹ̀ṣẹ́ wa wúlọ̀ fún gbígbà mọ́namọ́na làkòkò tó nrin àti ere sisa | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
TKWIS | Ọpọlọpọ awọn ilé ìtura wa ni lekki | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
OVFI5 | O n ṣe búrẹ́dì náà nínú ẹ̀rọ ayanran náà | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
0C0M3 | Àwọn olùkọ́ yóò lọ sí ìkọ́ṣẹ́ láti tún mọ̀ si nípa ìṣe olùkọ́ wọn ní àwọn osu | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
CSMDP | Kò sí oun tí ẹ ò lè fi ìrẹsì dá ní àrà. | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
V9M8W | Adé fẹ́ràn isẹ́ ìjọba nítorí owó rẹ̀ àti ìgbéga ipò rẹ̀ | yoruba | female | 6-17 | phase 1 | |
MOWN7 | Bẹ́ẹ̀ni, bàbá yóò ra ǹkan ìseré náà ní ilé ìtajà náà | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
NDET0 | ijoba tiwantiwa Titun ma to bẹrẹ | yoruba | female | 6-17 | phase 1 | |
SRYA7 | Àwọn òbí ilẹ̀ Áfíríkà kórira dírẹ́dilọọkì lórí àwọn ọmọkùnrin wọn. | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
BN1ZC | Mu ọkọ ayọkẹlẹ lọ si gareji! | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
LR4Z9 | Ààrẹ tí tẹ́lẹ̀ Mohammed Buhari ni adarí-ogun ẹ̀ka ogun ilẹ̀ Nàìjíríà tẹ́lẹ̀. | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
HZAHG | Titus ni órúkò sàdín ti mó jè làná | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
ZCZAL | Bẹ̀ẹ́ni, mo tí fọwọsi ìtọjú lẹyìn ibí ọmọ. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
V6MKF | O ní òun máa wọ agbádá aláǹkárá ní ọ̀la | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
0X1E0 | Oríṣiríṣi àwọn èèyàn pẹ̀lu oríṣiríṣi àwọn iṣẹ́ àti ipa ní a lè rí ní ọ́fìsì | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
OJ2WU | Ọ̀pọ̀ àwọn ènìyàn tí wọn wà lára àwọn ẹgbẹ́ ìkọ̀kọ̀ ni wọ́n pilẹ̀sẹ̀ fún un. | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
IF56O | Màá ra oúnjẹ fún olùkọ́ mi ni ìrọ̀lẹ́. | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
KJSW9 | Kérésìmesì ò ní pẹ́ dé. | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
XCBN0 | Ohun ẹlẹgẹ́ ni àwọn obìnrin jẹ́ | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
VAO6L | Mo fẹ́ lọ wo òòsà ẹ̀yọ̀ lọ́la | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
MZLHM | Awọn èèyàn sọrọ ní ilé agẹrun | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
22E62 | Awọn ọmọde n ṣere ni kicten | yoruba | female | 6-17 | phase 1 | |
S22CZ | Ǹjẹ́ orí tiktok kọ́ lo ti wo fọ́nrán yẹn? | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
P6R7R | Níàyé niétìsí; kọ sí ẹ̀rọ́ tii ń gẹ kọríkọ àyá fàdá | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
UVHS4 | Ikorodu ni mó ti rà awọn ìṣó yi | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
ZB24U | Aṣọ ìdámọ̀ àwọn nọ́ọ̀sì ni funfun àti búlúù | yoruba | male | 6-17 | phase 1 | |
V6MKF | Opolopo ènìyàn ni wọn ma ki bi ìnáwó bá ṣe ń lọ. | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
YQUQL | Kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ kò wọ́pọ̀ ni ìgboro mọ | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
4M562 | Mo ṣẹ̀ṣẹ̀ n padà dé lati ọjà ọta | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
6W1VG | Ní oṣù díè sẹ́yìn, ẹgbẹ́ òṣèlú APC ṣe àjọyọ̀ ìṣẹ́gun, nítorí pé wọ́n jáwé olúborí ní ìdìbò Ààrẹ orílè-èdè | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
AO5SO | Yorùbá kò mọ ohun tó ń jẹ́ òpó iná tẹ́lẹ̀ | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
9JXJF | Ilé ni a ti ń kó ẹ̀ṣọ́ r'òde jẹ́ òwe nípa ìwà ènìyàn. | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
W8MQ2 | Obìnrin náà sọ àwàdà mẹ́wàá | yoruba | female | 30-over | phase 2 | |
RNXAJ | Igi pọ̀ nínú igbó. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
WJCQL | Ìyá mi ti ra ọlọ tí màá fi máa lọ ata. | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
7TZW9 | Lọ́la kúndùn irọ́ ní ìṣẹ́jú-ìṣẹ́jú | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
18YYP | Go and report yourself to the head master. | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
E42L4 | Bàbá mi di èjìká mi mú nígbà tí ó rí mi lẹ́hìn ìpínyà ọdún marun. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
PMQ6H | Náírà márùn-ún ni wọ́n ń ta bisikí alágbòn lọ́pọ̀lọpọ̀ ọdún sẹ́yìn | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
KSYPO | Ògùn èló lo rà? | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
FYM3V | Arábìnrin bàbá mi ń gbé ní Àbújá. | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
Q6KV2 | Kí ni ó wà nínú ẹrù tí ó gbé sínú mọ́tọ̀. | yoruba | female | 30-over | phase 2 | |
6BYFH | Gbogbo ènìyàn gbọdọ̀ gba ilẹ̀kùn aloná koja ní ilé-ìfowópamọ́sí. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
IF56O | ògún kiloroquine ló wò pò jù ní lìló fún àìsàn ibà | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
V6MKF | Ọkọ mi rà àwọn ọ̀hùn tí a má n fi nú ara ọmọ tuntun lánà. | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
OVFI5 | Duro fun ìseju kan, Mo fẹ kun àtike mi | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
O0GW8 | Ṣé Kíkẹ́ ó gbé ẹ́rọ ìlọta wá lọ́la? | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
3VWIG | Ọ̀pọ̀lọpọ̀ èdè ni ó wà ní ilẹ̀ Yorùbá tí èdè Ọ̀yọ́ jẹ́ ojúlówó | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
4RPXR | A kìí lo abọ́ amọ̀ láti fi jẹun láyé òde òní. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
KY5I7 | A máa ń fi Ìṣebẹ̀ sí nu oúnjẹ fún adùn | yoruba | female | 30-over | phase 2 | |
OE4ZG | Njé olùkó gèésì ma kò wá lóni? | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
HNSNF | Obìnrin yẹn mú àwọn rẹ̀ lọ sí ilé-ìfowópamọ́sí ayánilówó alákọ̀bẹ̀rẹ̀ | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
WMEEI | A kì í pé olótùú rédíò nígbà kan. | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
JNYOA | Àwọn olóyè ma ń lọ sí òde náà pèlú ọba | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
MM9FZ | Ò̩pò̩lo̩pò̩ òwe, orin, ewì ni Yorùbá ní fún è̩kó̩ o̩mo̩ | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
F6X09 | Ọya kí oya àgbà nísìsiyìí! | yoruba | male | 6-17 | phase 1 | |
0FXWI | Ṣé olùkọ́ náà ń ko orúkọ àwọn akẹ́kọ̀ọ́ náà sinú ìwé orúkọ kílásì náà? | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
7GZIN | Ojú ọjọ́ yìí òjò ló máa fi rọ̀. | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
9CYPC | Àbúrò rẹ wipe kòkòrò náà kò dùn. | yoruba | male | 18-29 | phase 1 |
End of preview. Expand in Data Studio
README.md exists but content is empty.
- Downloads last month
- 11