audio
audio | speaker_id
string | text
string | language
string | gender
string | age_range
string | phase
string |
|---|---|---|---|---|---|---|
MZLHM
|
Ọpẹ́ yóò ra Panadol fún ọ.
|
yoruba
|
male
|
18-29
|
phase 2
|
|
3W24E
|
Iṣakoso iwe irinna idaniloju se idaniloju to dara ti awọn arinrin-ajo
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 1
|
|
II8KP
|
Báyọ̀ wà ní ẹgbẹ́ omi gbígbóná àti omi tútù ní Òndó
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 2
|
|
4XT0F
|
Àlọ àpagbè máa ń dùn.
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 2
|
|
E9RD1
|
Ọ̀gá àgbà pàdé rẹ̀ ní gbọ̀ngàn
|
yoruba
|
male
|
30-over
|
phase 1
|
|
MF6K9
|
Wọ́n má ń ṣe àfihàn àwọn orísìírísìí ohun ìṣẹ̀m̀báyé lórí orísun tẹ̀lifísàn
|
yoruba
|
female
|
30-over
|
phase 1
|
|
DK6MB
|
Àwọn olùkọ́ ní ìṣètò àkókò fún àwọn ẹ̀kọ́ wọn.
|
yoruba
|
male
|
18-29
|
phase 1
|
|
YP01K
|
Béèni o ti jẹ miang Kham tẹlẹ.
|
yoruba
|
female
|
30-over
|
phase 1
|
|
Q6KV2
|
Inú Odò ni wọ́n ti ń gún èlùbọ́
|
yoruba
|
female
|
30-over
|
phase 2
|
|
L88Q7
|
Pàlọ́ máa ń tóbi jù yàrá lọ
|
yoruba
|
male
|
30-over
|
phase 1
|
|
5Z6XO
|
Ọkọ òfurufú fúnni ní àlàáfíà ninu ìrìn àjò ju kẹkẹ lọ
|
yoruba
|
male
|
18-29
|
phase 1
|
|
HXQUJ
|
Mo gbàgbé láti fi omi sí nódùsì náà
|
yoruba
|
male
|
18-29
|
phase 1
|
|
LET8H
|
Bẹ́ẹ̀ni, màá ra sìpàgẹ́tì
|
yoruba
|
male
|
18-29
|
phase 1
|
|
JC6UM
|
Àwọn obìnrin náà ti wé gèlè
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 1
|
|
4XT0F
|
Yóò ṣíwọ́ lílo ògùn oyún lẹ́yìn tí ó bá bímo.
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 2
|
|
IKZHA
|
Béèni, orílẹ̀dè America dáràn genocide ní ìlú Hiroshima
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 1
|
|
O0GW8
|
Bẹ́ẹ̀ni ó lọ nọ́mbà kùpọ́ọ̀nù rẹ̀
|
yoruba
|
male
|
18-29
|
phase 2
|
|
7UZTO
|
Ní àsìkò Ramadan, àwọn Mùsùlùmí maá ń gbàwẹ̀ láti àárọ̀ títí dé òru.
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 1
|
|
DHWIH
|
Àwọn ènìyàn máa ń tèlé àwọn gbajúmọ̀ lórí ayélujára.
|
yoruba
|
male
|
30-over
|
phase 1
|
|
8K2XG
|
Ta ni ó ń ge koríko?
|
yoruba
|
male
|
18-29
|
phase 1
|
|
BI82X
|
Lẹ̀mọ́mú máa wá láti fún ọmọ náà lórúkọ ní ọ̀sẹ̀ tó ń bọ̀
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 1
|
|
COA80
|
Tọ́lá fẹ́ràn láti máa sọ ìtumò ìbéèrè aláròjinlè.
|
yoruba
|
male
|
30-over
|
phase 1
|
|
HNSNF
|
Ó yẹ kí ìjọba dẹ́kun ìṣọwọ́sọ̀rọ̀ àwọn nọ́ọ́sì sí aláìsàn lọ́jọ́ iwájú
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 2
|
|
QHCNI
|
ìjọba ológun lo tọ́ sí àwọn orílẹ̀ èdè kan.
|
yoruba
|
female
|
30-over
|
phase 1
|
|
QF5AT
|
Ishola yóò lẹ àwọn èso láti se ìtọjú wón .
|
yoruba
|
male
|
30-over
|
phase 1
|
|
VS6WC
|
Àlàbá ti pokùn so.
|
yoruba
|
female
|
30-over
|
phase 1
|
|
Q7FW1
|
Màá fi yé o̩mo̩ mi ló̩jó̩ iwájú pé yàrá às̩írí ni yàrá ibùsùn ló̩ko̩láya.
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 2
|
|
2QH6K
|
Mọ́tígájì báńkì máa ran ni lọ́wọ́ láti kọ́ ilé.
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 1
|
|
ZHR4X
|
Ẹ̀ka ìtajà báńkì yìí ni mo máa wà ní ọ̀sẹ̀ to ń bọ̀.
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 2
|
|
G4GLL
|
Níbo ni wọn gbé àpótí irinsé náà si?
|
yoruba
|
male
|
30-over
|
phase 1
|
|
EUP11
|
Ṣé o máa ṣe eré ìtàgé?
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 1
|
|
LRMKP
|
Àìná ni à ń sọ ọmọbinrin tó gbé ibi kọ́rùn wáyé.
|
yoruba
|
male
|
30-over
|
phase 1
|
|
43FB0
|
Ta ni ó lọ ra ẹ̀pà wá?
|
yoruba
|
female
|
30-over
|
phase 2
|
|
9SWNM
|
Atọrọjẹ kì í yó.
|
yoruba
|
male
|
18-29
|
phase 1
|
|
JH83R
|
Ibo lo ti pàdé Olú?
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 1
|
|
O4HRQ
|
Bàbá mi máa ń ṣàdúrà nínú yàrá wọn lójoojúmọ́ kí wọ́n tó jáde
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 1
|
|
V6MKF
|
Akápò na yóò wá wo isẹ rẹ wò
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 2
|
|
DBM3L
|
Ǹjẹ́ iṣẹ́ yàwúù-yàwúù pé ju iṣẹ́ ọmọlúwàbí lọ?
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 1
|
|
KSYPO
|
Ẹ̀wọ̀n àwọn ọmọdé ni wọ́n gbé ọmọ náà lọ
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 2
|
|
V6MKF
|
Akọsilẹ̀ ti a gbá ni áná jẹ̀ wahálà.
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 2
|
|
OJ8UO
|
Aṣọ aṣọ inura ngbanilaaye fun gbigbẹ irọrun ati ibi ipamọ ti awọn aṣọ inura
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 1
|
|
DMM7Q
|
Mo fẹ́ jẹ́ Akàròyìn àwòrán.
|
yoruba
|
male
|
30-over
|
phase 1
|
|
FDCBD
|
Àwọn ìbejì Táyọ̀ ó lọ Ọdún ìbejì ní Igbó-ọrà
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 1
|
|
KY5I7
|
Ṣè o ma lè dúró tì ọkùnrin ó ní ìpátá náà bá pa ẹnikẹ́ni lára àwọn mọ̀lẹ́bí rẹ̀
|
yoruba
|
female
|
30-over
|
phase 2
|
|
SRYA7
|
Adé bá aláàgbálùmọ́ náà sọ̀rọ̀ ní ọ̀sẹ̀ tó kọjá
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 2
|
|
WH65Z
|
Rárá, orò ìbejì ni wọ́n ṣe ní ọ̀sẹ̀ tó kọjá
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 1
|
|
P1DFA
|
mo wàá lọ Èkó láàárọ̀ yìí
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 1
|
|
FPAKJ
|
Kùkúmbà jẹ́ ohun ọ̀gbìn tó máa ń tètè dàgbà
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 1
|
|
31QDZ
|
O dára kí á máa mu omi.
|
yoruba
|
male
|
30-over
|
phase 1
|
|
59INZ
|
Iṣẹ́ abẹ ni Táyọ̀ fi bímọ
|
yoruba
|
male
|
18-29
|
phase 2
|
|
M9GTI
|
Rárá, àwọn ọmọdé ò le wakọ̀
|
yoruba
|
female
|
30-over
|
phase 1
|
|
I8Y7I
|
Onírúurú àwọn nǹkan ni à ń lò láti fi ka owó gẹ́gẹ́ bíi ọkà àti ìlẹ̀kẹ̀.
|
yoruba
|
female
|
30-over
|
phase 2
|
|
ZLOOP
|
Njé o ti rí àwòn tọkọtaya?
|
yoruba
|
male
|
18-29
|
phase 2
|
|
O0GW8
|
Olùrànlọ́wọ́ sọ́ọ́bù náà fún mi ní apẹ̀rẹ̀ ìrajà lánàá
|
yoruba
|
male
|
18-29
|
phase 2
|
|
4XT0F
|
Wọn kò ní mú àwọn ètò ní pàtàkì mọ́ nígbà àwọn ìran tó n bọ̀
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 2
|
|
2L5G3
|
Ràrá, olufisun náà ko ni sàn òwò beeli náà
|
yoruba
|
male
|
18-29
|
phase 1
|
|
UNW13
|
Ìtàkùrọ̀sọ lè wáyé láàárín èrò ọkọ̀ àti awakọ̀ , kọ̀ńdọ́kítọ̀ ọkọ̀ èrò tí a, wọ́
|
yoruba
|
male
|
18-29
|
phase 1
|
|
TTRXL
|
Oluwa Ibùdó ní Gbemi jé.
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 1
|
|
BXEDB
|
Lásìkò ìnáwó ìgbà yẹn, a máa ń mọ pàtàkì àwọn bàbá bàbá ilé àti àwọn ìyá ìyá ilé.
|
yoruba
|
female
|
6-17
|
phase 1
|
|
FRDIB
|
Bàbá àgbà pa àṣẹ pé Ṣadé kò gbọdọ̀ wu ìwà jàgídí-jàgan sí ẹ̀gbọ́n rẹ.
|
yoruba
|
male
|
18-29
|
phase 1
|
|
W8MQ2
|
Nọ́ọ̀sì náà lo stẹ́tósíkòpù láti ye lílù ọkàn mi wò ní àná
|
yoruba
|
female
|
30-over
|
phase 2
|
|
II8KP
|
Ṣàyẹ̀wò àwọn Ilẹ̀ oríṣiríṣi lónìí, ṣe àkíyèsí àwọn òkè-ńlá àti àwọn agbègbè alapin.
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 2
|
|
YWHBH
|
Àwọn Kristiani lọ sí ilẹ̀ ijọsìn ní Ọ̀jọ̀ Sundee
|
yoruba
|
female
|
30-over
|
phase 1
|
|
4RO3C
|
Pa kòkòrò na! Ìyá mi wí
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 1
|
|
V2BI9
|
Ìnágí làfí dàná làyé àtíjọ̀.
|
yoruba
|
male
|
30-over
|
phase 1
|
|
V6MKF
|
Ìyá mi máa ń mu èso lẹ́yìn tí wón bá jẹun tán.
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 2
|
|
7RWXR
|
o njẹ oúnjẹ àjèjì lónì .
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 1
|
|
G525B
|
Laipẹ̀, Ẹrìn kò ní wà ní Nàìjíríà mọ.
|
yoruba
|
female
|
6-17
|
phase 1
|
|
7OUSC
|
Yóò dára láti ní ẹ̀rọ amú omi gbóná ní inú pálọ̀.
|
yoruba
|
male
|
18-29
|
phase 1
|
|
Z5WFL
|
Adé máa jí se ìrẹsì lọ́tùn-únla
|
yoruba
|
male
|
18-29
|
phase 1
|
|
0F94V
|
Ṣé bàbá re le è san owó ilé ìwé rẹ
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 1
|
|
38CRD
|
Àwọn ará ìlú máa ṣe ọdún iṣu wọn ní gbàgede ìlú.
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 1
|
|
OHY27
|
Lo kóró kan!
|
yoruba
|
male
|
18-29
|
phase 1
|
|
ZHR4X
|
Mo lọ si igbeyawo sooṣi kan ni oṣu to kọja
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 2
|
|
LOISH
|
Oorùn ẹ̀yìn ọrùn mi ti pòọ́rá.
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 1
|
|
HZM4L
|
Flyover jẹ́ afárá tó fàyè gba àwọn ọkọ̀ láti sọdá lọ sí òdì kejì.
|
yoruba
|
female
|
30-over
|
phase 2
|
|
4XT0F
|
sùpàgẹ́tì ní oúnjẹ àyò rẹ̀
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 2
|
|
EQ2IN
|
Kíkẹ́ sọ pé, Olóòtú náà ti ṣàyẹ̀wò iṣẹ́ náà tán
|
yoruba
|
male
|
18-29
|
phase 1
|
|
DJ3BB
|
Ẹnikẹ́ni tó bá mọ̀ọ́mọ̀ pa ènìyàn yóò gba ìdájọ́ ikú nílẹ̀ Nàìjíríà.
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 1
|
|
OYG89
|
Ko yẹ ki o fún ọmọ yẹn ni oúnjẹ púpọ jẹ.
|
yoruba
|
male
|
18-29
|
phase 1
|
|
ZAFUM
|
Ṣọ́ọ̀ṣì náà ní àkátì mẹ́ta lórí ẹ̀rọ ayélujára.
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 1
|
|
SGO1V
|
Ìyẹn tí bàbá rẹ ò bá sí nílé.
|
yoruba
|
male
|
18-29
|
phase 1
|
|
2DBMP
|
Ọ̀pọ̀ ẹ̀mí ló ṣòfò lásìkò àrùn Korona
|
yoruba
|
female
|
30-over
|
phase 1
|
|
UP4RQ
|
Eewọ lati mu siga ni ọfiisi mi
|
yoruba
|
female
|
30-over
|
phase 1
|
|
KY5I7
|
Ilé-ìfowópamọ́ yìí ní ju ẹ̀rọ-ìkawó mẹ́ta lọ.
|
yoruba
|
female
|
30-over
|
phase 2
|
|
BN1ZC
|
Ṣóbọ̀wálé ń ra ámà tí ọkọ rẹ̀ nílò lọ́wọ́
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 2
|
|
HUR4D
|
Ogun Àgbáyé II kan ìjà ogun àgbáyé láti ọ̀kan-dín-ní-ojì lé ní ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ́wá sí ẹ́ẹdógún-dín-ní-ọ́ta lé ní ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ́wá
|
yoruba
|
female
|
30-over
|
phase 1
|
|
Q54MY
|
Biba àwọn ẹlomiran lelẹ ko tọ.
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 2
|
|
8K2XG
|
Taàní ó ń ka ìwé ìròyìn lọ́wọ́?
|
yoruba
|
male
|
18-29
|
phase 1
|
|
646RI
|
Ìyá Bísí máa ń gbọ́ ìròyìn lórí rédíò lójoojúmọ́
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 1
|
|
HNSNF
|
Àwọn mẹ́wàá ló máa sáré níbi ìdíje eré sísá náà.
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 2
|
|
HH0CR
|
Gègé ìkọ̀wé Pupa ni olùkọ́ wa fi máàkì iṣẹ́ mi lánàá
|
yoruba
|
male
|
18-29
|
phase 2
|
|
7RJMD
|
Rárá, mi ò ní wọ ọkọ̀ ojúrin náà lọ sí abúlé náà
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 1
|
|
IF56O
|
Òkúnrin ólóyé yèn n bò lòsè tó n bò
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 2
|
|
IXW8R
|
ọkọ mi yóò mú pana bọ̀ nígbàtí ó bá ń bọ̀ .
|
yoruba
|
female
|
6-17
|
phase 1
|
|
XPEKN
|
Ṣé wà á ra ọsàn fún mi?
|
yoruba
|
female
|
30-over
|
phase 1
|
|
YDSCH
|
Awọn eniyan ṣafihan awọn igbesi aye ikọkọ wọn lori sósia midiya
|
yoruba
|
male
|
30-over
|
phase 1
|
|
LM2IX
|
Ọbẹ̀ kìí mì ní ikùn àgbà
|
yoruba
|
female
|
30-over
|
phase 1
|
|
0F94V
|
Àìsàn jẹjẹrẹ kò ní ìwòsàn.
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 1
|
|
01KHE
|
Rárá, emi kò sanwọ fún ríran aṣọ nṣa
|
yoruba
|
male
|
30-over
|
phase 1
|
End of preview. Expand
in Data Studio
README.md exists but content is empty.
- Downloads last month
- 2