audio audioduration (s) 0.06 23.3 | speaker_id stringlengths 5 5 | text stringlengths 6 184 | language stringclasses 1
value | gender stringclasses 2
values | age_range stringclasses 3
values | phase stringclasses 2
values |
|---|---|---|---|---|---|---|
HPTGN | Alágbẹ̀dẹ náà sọ pé òun má wá ní ọ̀la | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
GF0ZT | Ìbálòpọ̀ láàrin àwọn ọmọ Ìyá àti Bàbá kan náà ni Áfríkà. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
HZM4L | Bẹ́ẹ̀ni, wọ́n ti ṣe òkú náà tan. | yoruba | female | 30-over | phase 2 | |
I18DW | Oríṣiríṣi ìsebẹ́ ni a ní, ní ilẹ́ Yorùbá | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
LCOS2 | ìgbà wo ló wọ gẹ́tò? | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
HZM4L | Ojú gbòòrò ni à ń kìí onídìrì ni ilẹ̀ Yorùbá. | yoruba | female | 30-over | phase 2 | |
ZLOOP | Ka àwọn àwọ̀ náà báyìí | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
KSYPO | Alawada ni bàbá Suwe | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
BKZJV | Ṣé wàá gbé ipò kejì? | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
BNHWM | Ìgbà wo ni wón ṣe ayẹyẹ ọdún Sàngó? | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
OVFI5 | Ṣe o tí dé láti àgbò oògùn lola? | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
JCGP7 | A o fi ìrọrí onífo sókè ṣeré | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
4B434 | Dambe sì jẹ́ ara ẹkẹ mímu ó sì ti abágbàmu | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
3ZLV0 | Ẹgbẹ́ olórín kan ni 2face, Black Face àti Face Alone wà kí wọn tó pínyà | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
Q6KV2 | Awọn ipa wo ni awọn ọmọde yoo ṣe ni ile? | yoruba | female | 30-over | phase 2 | |
SZL2L | Yóò pàdé ọkọ̀ rẹ̀ ní ọgbà-ìṣeré | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
SRYA7 | Oníṣòwò kan ta ọjà ní ọjà lánàá, tí ó ń fa ọ̀pọ̀lọpọ̀ oníbàárà mọ́ra. | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
IF56O | Wòn má n tá áwòn nkán tò kówá láti óké ókún ninú ilé òjá nlá | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
7VUZF | Bẹ́ẹ̀ni, mo fi àdá gé àwọn ẹ̀ka igi náà. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
KGKZ4 | Mo sọ ọmọ mi ní Ọ̀jẹ́wálé nítorí ìdílé eléégún ni ọkọọ̀ mí | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
28CXH | Dayo kọ́ fílátì òní yàrá ibùsùn mẹ́ta ní èkó | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
L1UR5 | Awọn ẹrọ kika awọn banki ko ṣiṣẹ | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
BOY4H | Iná ẹ̀yìn Kúnlé kìlọ̀ fún àwọn awakọ̀ tó ń bọ̀ lẹ́yìn rẹ̀. | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
LFWC9 | O gbọ́dọ̀ ra ológbò fún ọmọ rẹ lọ́la! | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
97RE4 | Múrí Márùn-ún ní kọ̀ọ̀kan Núdúsì yìí | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
D1LUP | Àwọn olùrànilọ́wọ̀ ni àwọn ènìyàn tó ń ṣe ìràwọ̀ lágbègbè ilé ẹ̀kọ́ bíi aṣọ́gbà tàbí akọ̀wé | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
SQKKM | Gbé kẹ̀kẹ́ mi wọ inú ilé lọ | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
LNXWF | Ojúbọ jẹ́ ibi mímọ́ tí ó wà fún òrìṣà tàbí ẹ̀mí kan pàtó. | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
YHWAH | Omi ń yọ nínú ilé igbonse mi | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
Q7FW1 | Mo lérò pé ojúṣe ayeìwéwò ni láti yẹ àkántì báńkì. | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
LA0Y9 | Ẹran yíyan tí ìyá mi fún mí láta púpọ̀ | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
CGXXR | Òun ló kéwì. | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
UC79S | Olu kọ ọfọ̀ sínú ìwé | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
COA80 | Tólá mú páńpásì náà wà | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
SRYA7 | Òlòngbó jẹ́ ẹ̀raǹkò tí o ńgbẹ̀ ní ilẹ̀ pẹ̀lu wà | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
MQ3OG | Àwọn ọ̀rẹ́ míì máa ń padà di ẹbí | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
D84K6 | Àyípadà nbè fún talika, olówó ní ko lòó ṣora | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
4GHNH | Fọ́ ọmọdékùnrin náà ní etí! Yóò pàṣẹ | yoruba | female | 6-17 | phase 1 | |
OHV0R | Àwọn ọmọ ìyá le máa jowú ara wọn | yoruba | female | 6-17 | phase 1 | |
59INZ | Mà á di afró lọ́la | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
IF56O | Ṣé a máa fìwé pe akẹ́kọ̀ọ́ náà? | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
DQIRE | Wọ́n yóò kọ̀ abúlẹ̀ fẹyíntí ní Ikọ́tun Lagos laípè. | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
QF3L3 | Bọla, lo fítámìn E lati fi dènà ẹjẹ dídì . | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
2WJTR | Ó gbọ́dọ̀ gbé pẹlú ìdílé bàbá à mi! | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
HZM4L | Adio má ń bọ orí lóṣoosù | yoruba | female | 30-over | phase 2 | |
MGWAM | Adépọ̀jù kọrin daada ní àná | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
2VGOD | Afọ́jú ń rìn lọ inú ọjà | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
43FB0 | Tani yóò lọ aṣọ ìdánimọ̀ mi? | yoruba | female | 30-over | phase 2 | |
TQKTS | Iwájú ilé ni ojúbọ Obatala náà wà. | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
LET8H | Egusi àti ìgbín dára púpọ̀ | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
0K8VZ | Ètò òṣèlú máa ń le ni àsìkò ìdìbò | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
TL0SY | Taló máa ṣe ìgbọràn sí gbogbo àwọn òfin náà? | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
OZCG2 | Irun gíge kí í wọ́pọ̀ láàárín àwọn obìnrin láàyè àtijó. | yoruba | female | 30-over | phase 2 | |
WUSNO | Mrs Kofo ń jẹun nínú yàrá àwọn olùkọ́. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
IUWY6 | Akin kò fẹ́ràn arákùnrin-ìyá rẹ̀ nítorí ó lárun. | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
GNC5Y | Wòn fún wá ni iwé àkójò èrú iyáwó làná | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
QF1OT | ọlọrun dá mi ní àwọ̀ tí mo fẹ́ràn | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
38CRD | Ẹkùn ni o pá ọ̀bọ naa | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
KE3A6 | Ọ̀nà míràn fún okoòwò ni nípa ìsura pípàrọ̀ | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
JR5WW | Sọkẹ̀tí iganna máa n wà lára ògiri inú yàrá kọọkan nínú ilé. | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
ZZ7JJ | àlúwalá olońgbo, ogbọn atí kerán je | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
YQROM | Àwọn ọ̀kín máa ń ní ìyé aláràbarà | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
TVXJ7 | Wọ́n máa bẹ́ orí ajá lọ́jọ́ ọdún ògún. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
I1W1C | À yòó rọ́pọ̀ awọn bẹẹ̀tù ní lààbù ìṣẹ̀dáilé | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
3CDW5 | Iru tubu kọọkan ni awọn ọna aabo oriṣiriṣi ati awọn ilana | yoruba | female | 6-17 | phase 1 | |
NJEWX | Ṣé o gun afárá náà lánàá? | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
2WJTR | Ṣé o ti wo àwọn àwòrán fọ́nrán náà | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
CSMDP | Igi le di ohun ìdáná, pákó le di ohun furniture. | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
TOZM7 | Ní ìwòn odún marun si isínsìnyí, mo gòkè nínú isẹ́ mi, mo si fe ririnajo lo sí àwon orílẹ̀dè sí | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
RWUNS | Atukọ̀ ní yóò darí ọkọ̀-ojú-omi | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
ELC7E | Aṣọ jè kóṣémáni fùn éniyán | yoruba | male | 30-over | phase 2 | |
FO18W | Akó ìwé kọ́ọ̀tù pamọ́ kọ̀ láti sọ̀rọ̀ lórí ìṣẹ̀lẹ̀ náà | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
0X1E0 | Orò ìdílé àwọn Tọ́lá ló mu kí ìyàwó àfẹ́sọ́nà rẹ̀ fi sílẹ̀. | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
2WJTR | Ojú tó bá máa báni kalẹ́, kìí tàárọ̀ ṣepin ni òwe tí ènìyàn ń lò lati ìyípadà ìwà ẹ̀dá | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
4XT0F | Ẹgbẹ̀rin-dín-méjì ni tíkẹ̀ẹ̀tì tí wọ́n ma tà ní ètò náà ní oṣù Agẹmọ | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
XIG19 | Mo máa di ẹnjiníà lọ́jọ́ ọ̀la. | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
SEDW4 | Ẹgbẹ́ ọ̀dọ́ ń ṣe ìpàdé lórí bí ìlú ṣé ń lọ | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
MGWAM | Páàkì ọkọ̀ síbi tó dára | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
24ZOQ | O yi ina yẹn sílẹ. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
YPLJE | Àdìgún ni ó ra sìgá. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
GNC5Y | wọ́n pa ọ̀pọ̀lọpọ̀ “ ọ̀kẹ́rẹ́”. | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
0TGK3 | Ṣé o ní kọ́mú? | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
U09PH | Êàê òóò ñîâñåì íåò íè÷åãî. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
QCVFY | Jẹjẹrẹ ni ó pa obìnrin náà! | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
9OB30 | Bayo fẹ́ yá mílíọ̀nù mẹwa ní microfinance bank. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
DN5E8 | Bẹ̀ẹ́ni, mọ ní àwọn aṣọ títún diẹ. | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
0CXKQ | Ẹ̀rọ ibanisoro ti Ìyàrá igbalejo nko? | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
UAVQC | Ṣé o lè jẹ ọbẹ̀ ewúro? | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
XL6JK | Ilẹ̀-ìṣẹ̀ náà fún awọn oṣiṣẹ̀ wọn ni àṣọ tuntun ni ọṣẹ̀ tó kọja | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
Q7FW1 | Rárá, Mi ò lò ó, kílíìpù ni mo lò. | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
1A5ZC | Wọ́n ṣẹ̀ṣẹ̀ gbá apààyàn kan mú ni | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
L6YRG | Àwọn obìnrin fẹ́ràn láti ma ṣe ojú wọn lóge. | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
QLGXT | Báwo ni ọmọ rẹ ṣe tóbi tó nígbà tí o bíi? | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
O0GW8 | Flagyl ni a maa n lo fun gbuuru ni Nigeria. | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
JDR85 | Bólú yóò rìnrìn-àjò nípasẹ̀ ọkọ̀ ojú-omi lọ́jọ́ ajé. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
K3KLM | Ọbẹ̀ kìí mì inú àgbà | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
HH0CR | Òní ni àbíkẹ́yìn wa fẹ́ jáde ní ilé-ẹ̀kọ́ alákọ́bẹ̀rẹ̀ | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
SKABL | Akukọ ti o wa ninu ile mi ṣe ifamọra iyawo rẹ nipasẹ ogbe pupa rẹ | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
Z9ZVR | Nígbà wón ní wà wọ ilẹ̀ mi? | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
K0YIP | Mo rí láìpé níbi tábìlì ìbánisọ̀rọ̀ | yoruba | male | 18-29 | phase 1 |
End of preview. Expand in Data Studio
README.md exists but content is empty.
- Downloads last month
- 14