audio audioduration (s) 0.06 23.5 | speaker_id stringlengths 5 5 | text stringlengths 4 170 | language stringclasses 1
value | gender stringclasses 2
values | age_range stringclasses 3
values | phase stringclasses 2
values |
|---|---|---|---|---|---|---|
777UH | Gàrí àtí ómí gbigbónà lò fí n tè èbà | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
O0GW8 | Mà á mú ẹfun wá lọ́la | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
I9T60 | Olùkọ́ àgbà náà yóò gba àwọn akẹ́kọ̀ọ́ náà níyànjú ní ọ̀la | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
ELC7E | Awòn ògèdè àgbágbá má n tóbí jú áwòn ògèdè lò | yoruba | male | 30-over | phase 2 | |
AMFTP | Ọ̀gá ńlá máa dá sẹ̀ríà fún àwọn ọmọdékùnrin náà ní ọ̀la | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
JL8Y6 | Bolanle kò finú tọ́ ẹnìkankan pẹ̀lú owó rẹ̀. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
PWN0T | Gbọ̀ngàn ohun-ìṣẹ̀m̀báyé tí wọ́n fi sọrí ilé ìyàgbẹ́ jẹ́ ni ilékọ̀ọ́ ìṣegbọ̀nsẹ̀ jé. | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
SRYA7 | Adésẹwà n fọ aṣọ àrẹ̀mọ | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
QBWT6 | We saw a Leopard in the forest | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
755YF | Sa ẹ̀pà náà kí o tó yan án ní ọ̀la. | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
VUV3K | Mo sọ wípé ohun asẹnti British sí lẹ̀. | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
KV6O3 | Tani yoo ra aṣọ tuntun kan? | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
AGDH6 | Ní àná, àwọn ènìyàn gbé ọkọ̀ ayọ́kẹ́lẹ́ wọn síta | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
PWHG3 | Bọ́lá fẹ́ máa kọ ìṣe kunjúkunjú àti gèlè wíwé | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
ZHR4X | Mo wúre fún ọmọ mi lánàá. | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
FPLVR | Kiri ibẹ́pẹ lọ s'ọ́jà Yábàá. | yoruba | female | 6-17 | phase 1 | |
H1DJ8 | A mọ ọjà Mile 2 sí ọjà èso | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
P42DO | High jump jẹ́ ọ̀kan lára àwọn eré ìdárayá ilé ìwé. | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
M6SAQ | Ìsòrí ẹka ẹ̀kọ́ igbó ni mo kọ́kọ́ lọ. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
Q7FW1 | Mo gbódò ra àwọn òdòdó kan ní ọ̀la | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
33QY9 | Kíkọ́ yàrá kékeré lè fa ooru. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
O4Q43 | Mi ò le lo ẹ̀rọ gáàsì nígbà tí mò ń dáná ní alẹ́ àná nítorí pé gáàsì ti wọ́n | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
RUYB2 | A máa ń ní olóòtú nínú ilé iṣẹ́ ìtẹ̀wẹ́. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
Z2Q9X | Ọjọ́rú ni wọ́n máa ń ná ọjà Sabo nílùú Ikorodu | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
UHRQX | Fọlá jẹ úgú náà? | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
JNHHS | Darapọ̀ mọ ẹgbẹ́ òṣèlú kàn! | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
MAZXB | Mo ra tòmátò ni kan | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
AJUQK | Awọn ododo le ṣee lo lati ṣe afihan aanu tabi itunu | yoruba | female | 6-17 | phase 1 | |
Z9ZVR | Nígbàwọ̀ ni iwọ yóò bẹ̀rẹ̀ ipilẹ̀ ilẹ̀ náà? | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
M1KTP | Àwọn ilé ìwé máa n fún àwọn akẹ́kọ̀ọ́ wọn ni kúkísí Oreos lásìkò ìsinmi. | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
8EF3R | Bẹ́ẹ̀ni, mo wà lórí facebook | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
JQPJE | John fè tá Ẹ̀rọ ìtẹ̀wé nla rẹ. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
VUGDK | Mo ma fin àwon eja yen lọ́la | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
HN1Q2 | Ẹgbẹ́ náà ó yan adarí tuntun lọ́la | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
F76OQ | Lọ gbálẹ̀ yàrá ìbùsùn rẹ! | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
4XT0F | Sáyẹnsì yóò sí fè ojú ìsèdálè. | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
Q7FW1 | Mo mùka dàgbà ni | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
V6MKF | Ó wí pé, "nu ilé-ìgbọ̀nsẹ̀ yẹn" | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
GLELE | Ọjà ohun èlò ìkọ́lé ni a má ti ń ra ohun èlò ìkọ́lé | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
2SCF8 | Àwọn ilé alámọ̀ wọ́pọ̀ láàárin àwọn Yorùbá láyé àtijó. | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
MJDNG | Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ kó àwọn ìlù tuntun wọ yàrá ìlù | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
JC6UM | Ṣé ìyá rẹ wá fún ìpàdé? | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
YT0T2 | Gbígba yàrá kò wón tó gbígba ilé ìtura lọ | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
TGB73 | Taye jẹ ìrẹsì lálẹ́ àná | yoruba | female | 6-17 | phase 1 | |
W8MQ2 | Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ náà seré ní orí pápá bọ́ọ̀lù-alágbọ̀n náà | yoruba | female | 30-over | phase 2 | |
SOZO0 | Ṣé ẹ máa kọrin yìí lọ́la? | yoruba | female | 6-17 | phase 1 | |
43FB0 | Bẹẹni, mo ń nu àwọn nkan ti a fi ń roko. | yoruba | female | 30-over | phase 2 | |
BN1ZC | Ibi ìseré tó wà ní Ìbàdàn yóò ṣí nígbà kérésìmesì | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
28VR6 | Ìtẹ̀síwájú ìmọ́ ni sise onje mu ònà ìdáná ti yio yi bi a ti n se ounje padà | yoruba | female | 6-17 | phase 1 | |
2VGOD | Ìgbágbọ́ àwọn yorùbá ni pé àwọn ènìyàn kì í kú, wọ́n máa ń pa ipò dà ni. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
SRYA7 | Adé yóò ra èédú fún ìyá rẹ̀. | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
C4FXB | Àti kékeré lati ń pẹ̀ka ìrókò, torí tó bá dàgbà tán ẹbọ ni yóò ma gbà. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
2HRJ7 | Mà á lo oògùn ara ríro tí mi ò bá wà pa. | yoruba | male | 6-17 | phase 1 | |
HIAR2 | Wọn yẹgi ikú fún apànìyàn náà. | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
6BSDR | Mo máa fi Face Time bá Ẹ̀gbọ́n mi lékòó sọ̀rọ̀ lọ́la. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
SQKKM | Wọ̀sìwọ́sì kò le dínkù láàrin àwọn ìpẹ́ẹ́rẹ́ lọ́dún márùn-ún sí òní | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
F9VON | Ọmọ ọwọ́ ni Ọpẹ́ nítorí náà kò sí ní ẹgbẹ́ kankan. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
L3928 | Ará Irun fìlà ọlọ́pàá náà dàbí fìlà ọlọ́pàá ni tòótọ. | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
3KBAT | Óríkì jè Éwì Alóhùn | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
G3ZEL | Ẹ mélòó ni ó máa ń kí bàbá rẹ ní ojoojúmọ́? | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
QFQSP | Ọda jẹ nkan olomi ti a lo fun kikun | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
U7LKC | Ìyá Kọ́lá tí wá ojútùú sí ìṣòro náà. | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
II8KP | Wọ́n ń fi gíláàsì alábò fi ṣe gilaasi ọkọ̀ láti dín ewu Ìjàmbá kù | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
W8MQ2 | Ẹka aabo wa lori iṣọ làná | yoruba | female | 30-over | phase 2 | |
DULER | Ibẹ̀rẹ̀kì alùpùpù náà burú ní ọ̀sẹ̀ tó kọjá. | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
4FR3A | Àìsàn lè wáyé latari pé aifọ ọwọ pẹlú ọsẹ àti omi lẹyìn lilo ilé igbọnsẹ. | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
MZLHM | Ẹ̀yà irun pátèwọ jé ẹyà Irun ti wón hùn . | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
EU5R7 | Búrékì máa ń ran ọkọ̀ lọ́wọ́ láti dúró nígbàkigbà tí awakọ̀ bá fẹ́ kí ó dúró. | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
VVKH2 | Àwọn èrò ọkọ̀ kú sínú ìjàmbá ọkọ̀ | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
Z9ZVR | Nigbawo ni a yoo de ibi iduro ọkọ akero? | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
ZLOOP | njé Ọkọ rẹ ra àpótí òún èló ìkunjú fún ? | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
OZCG2 | Ṣé ọmọ yẹn Lẹ́kọ̀ọ́? | yoruba | female | 30-over | phase 2 | |
3TUIS | Ni ilẹ̀ Yorùbá, ọkùnrin lo máa ń jọba. | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
95SWE | Fóònù rẹ̀ jẹ́ aláwọ̀ búúlù dúdú | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
S6GMD | Àwọn olóyè ìmọ́tótó máa ń rí i dájú pé ìmọ́tótó wà ní gbogbo ilé-ìwé. | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
D10NS | Adé yóò ṣètò láti lọ síbi íkọ́ni bí a ti ń dirun fún àwọn onídìrí | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
PH979 | Mo fi kofilini náà sínú ìgò ọtí òyìnbó fún ọmọ mi. | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
KPMTF | Nínú ẹgbẹ́ akọrin a máà ń ní fèrè meji sí mẹrin. | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
PMRNX | Ta ni ó lo ìfọyín tó wà lóri tàbílì yẹn? | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
PDK5R | Ṣé ẹjọ́ ń lé ẹ ní? | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
97RE4 | Kí ni orúkọ ilé ìfowópamọ́ rẹ yóò jẹ́? | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
KJSW9 | A ń bọ Ẹ̀sù. | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
LA0Y9 | Ẹyin wà nínú eggroll. | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
G1ERL | Arábìnrin náà ti ní ẹjẹ rírú látara pé o máa n páríwó mọ àwọn èèyàn. | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
NK5AO | Béèni wón ní Agolo ẹlẹ́nu gígùn fún bíbomirin ọgbà títún. | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
LA0Y9 | Inúu ẹ̀rọ amóhuntutù ni a ti gbé ẹran náà jáde. | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
KSYPO | Wọn gbé ìyàwó ọrẹ mi lọ sí ilé ìtura àwọn onímọ́tò | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
UU64O | Àwọn ọ̀mọ̀wé fẹ́ràn láti máa jẹ búrẹ́dì àti ẹyin díndín | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
VE5CF | Orísìírísìí ìdílé ló ní òye tí wọ́n ń jẹ ní ìdílé wọn | yoruba | female | 6-17 | phase 1 | |
IF56O | Ábò ni ibi ti áwòn òkòójùómì má n gúnlé si lébùté | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
CSMDP | Ìkirè lọ́ ti ń ṣe dòdò Ìkirè. | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
Q54MY | Kola fí ewé Moringa ṣe ìtọjú Jejere. | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
VAO6L | Ìbálòpọ̀ orí fóònù kòsí ní àwọn ọdún díẹ̀ sẹ́yìn | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
CS8TB | Kini órúkò èjà ti ó rá làná? | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
K3KLM | Olùkọ́ ìmọ̀ àwùjọ yóò máa kọ́ni lórí àkọlé "ìmọ̀lára" | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
VAO6L | Maṣe gbiyanju lati mu ṣiṣẹ pẹlu kọnputa naa | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
UP4RQ | Ilé ẹni la tí ń jẹ òkété onídodo. | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
CXNLY | Àwọn èrò tí pọ̀ ní ilé ìdìbò. | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
HH0CR | Bàbá mi fẹ́ràn ìṣèjọba onísọdọ̀kan | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
SKABL | Ṣiṣe ikoko gba sũru pupọ | yoruba | female | 18-29 | phase 1 |
End of preview. Expand in Data Studio
README.md exists but content is empty.
- Downloads last month
- 9