Dataset Viewer
Auto-converted to Parquet Duplicate
audio
audio
speaker_id
string
text
string
language
string
gender
string
age_range
string
phase
string
D10NS
Fìlà ọlọ́pàá ni irun ti wón pè ní ilé ìwé won
yoruba
female
18-29
phase 1
LET8H
Ewédú ní ọbẹ̀ Yorùbá tí ó gbajúmọ̀ jù tí wọ́n ń fi oríṣiríṣi òkèlè tì í.
yoruba
male
18-29
phase 1
HPTGN
Ṣe iwadii pataki itan ti awọn ilana ipilẹṣẹ egbeokunkun ni awọn awujọ atijọ
yoruba
female
18-29
phase 2
Q6KV2
A lo àgé-onípáànù láti fi bomi-rin ohun ọ̀gbìn.
yoruba
female
30-over
phase 2
HZM4L
3. Mi o rántí irú egbògi tí títí lò.
yoruba
female
30-over
phase 2
OYBT6
O gbodò gun igi yan
yoruba
male
18-29
phase 1
CIUZC
Ọmọdébìnrin náà ti wọ inú ayé òwò nàbì.
yoruba
female
18-29
phase 1
HZM4L
Ẹ̀wọ̀n gbére ni wọn máa ń fún ẹni tí ó bá pa ènìyàn.
yoruba
female
30-over
phase 2
7T1HD
Lọ sí awọn ilé-ìwé olukọni rẹ! Igbákejì Alàkóso sọ fun awọn ọmọ ilé-ìwé
yoruba
female
6-17
phase 1
CGQWW
Pa tẹlifisiọnuBenga paṣẹ
yoruba
female
18-29
phase 1
XH11B
Yóò gba owó láti ẹnu ẹ̀ro ìgbowó ní ọ̀la
yoruba
male
18-29
phase 1
TL2B1
Olùkọ́ kan ṣe ìdánilẹ́kọ̀ọ́ fún àwọn ọmọbìnrin lórí ọgbọ́n ìdarí.
yoruba
female
18-29
phase 1
8HDWA
Bísí wà ní fakọọti ti óníse pẹ̀lú ìhùwàsí àwọn ènìyàn ní ìṣẹ́jú tí ó kọjá díẹ̀ sẹ́yìn
yoruba
male
18-29
phase 1
O6E7Y
Yes, we will Foundation be needed for oily faces
yoruba
male
30-over
phase 1
YT0T2
Bíbùnkún fún ènìyàn dára jọjọ.
yoruba
male
18-29
phase 2
ZEDKI
Óòtọ́ ni ádùrá yóò má ń tẹ́lè ìkíni ní ilé Yorùbá
yoruba
female
18-29
phase 1
F9VON
Ọpẹ́ jẹ́ adarí ọlọ́rọ̀.
yoruba
female
18-29
phase 1
DHWIH
Rárá, òun yóò ṣe àbẹ̀wò sí àbúrò bàbá rẹ̀ ní ilé ìtọ́jú àwọn arúgbó.
yoruba
male
30-over
phase 1
WDLJK
Bẹ́ẹ̀ ni àwọn yàrá ńlá ńlá wà fún àwọn ènìyàn ńlá tí ó bá bá ilé ìtura ní àlejò
yoruba
female
18-29
phase 1
WHAH7
Ẹka ti Gẹẹsi ati Awọn Ijinlẹ Litireso ṣawari ọpọlọpọ awọn oriṣi iwe-kikọ ati awọn ẹkọ-ede
yoruba
female
30-over
phase 1
HZM4L
Iwọ yóò wá èèrà ti o bù mí jẹ!
yoruba
female
30-over
phase 2
W8MQ2
Àwọn aṣojú akẹ́kọ̀ọ́ ní ilé-ìwé máa ń wà ní ìmọ́tótó.
yoruba
female
30-over
phase 2
TOZM7
Ninu àwọn ìtan-ẹ̀ranko, àwọn ẹ̀ranko ni aǹlo làti kẹkọ iwa.
yoruba
male
18-29
phase 1
05HN6
Ta ló fẹ́ jẹ sùpàgẹ́tì?
yoruba
male
18-29
phase 1
ELC7E
Àná ni iyáwó mi dé
yoruba
male
30-over
phase 2
0YVR9
Ǹjẹ́ mo ní láti gbàgbọ́ nínú ẹ̀sìn kí n tó le jẹ́ ẹ̀yàn rere?
yoruba
female
30-over
phase 1
6YN03
Bẹ́ẹ̀ni, mo lọ sí ọdún Òkè Ìbàdàn ní ọdún tó kọjá
yoruba
female
18-29
phase 1
IRDAD
Àkànní yóò ra oúnjẹ tí ó tó iye múrí márùn-ún.
yoruba
male
18-29
phase 1
Q7FW1
Mo máa ma rí orí àwọn ọ̀pẹ òyìnbó tí mo fẹ́ lò fún ọ̀gbìn ni ọjà.
yoruba
female
18-29
phase 2
L88Q7
Ọba tàbí obìnrin-ọba ni olórí ìlú lábẹ́ ètò ìṣèjọba ọlọ́ba.
yoruba
female
30-over
phase 1
OHY27
Fáítámì B ṣe àlékún àwọn iṣẹ ètò àìfọkanbalẹ̀
yoruba
male
18-29
phase 1
ZNH22
Mo jẹ ìrèké lánàá
yoruba
female
18-29
phase 1
II8KP
Alagbẹdẹ lo n ṣe ada, awọn ọbẹ ati awọn gige irin miiran
yoruba
female
18-29
phase 2
OVFI5
Ǹjẹ́ o ti tọ́ ẹmu wò rí?
yoruba
female
18-29
phase 2
UVEJ2
Òpọ̀lọpọ̀ àwọn àpá ní pápá ọkọ̀ òfurufú ní.
yoruba
female
30-over
phase 1
HZ67C
GRA ni a nireti lati tẹsiwaju idagbasoke bi agbegbe idagbasoke ilu awoṣe
yoruba
female
18-29
phase 1
KSYPO
Ìjọba oloba aládé ni orílẹ̀ èdè Saudi ń lò
yoruba
female
18-29
phase 2
MM9FZ
Obìnrin náà yóò se ọbẹ̀ ẹ̀fọ́ fún gbogbo ènìyàn.
yoruba
female
18-29
phase 1
MMOKX
Ọjọ́ wo ni ìjókòó mọ̀mí-n-mọ̀-ọ́?
yoruba
male
18-29
phase 1
MZLHM
Àsìkò ìjọba ológun ti ọ̀gágu Murtala Muhammed àti ọ̀gágun Olúṣẹ́gun Ọbasanjo ní wọ́n dá ìpínlẹ̀ Ogùn sílẹ̀.
yoruba
male
18-29
phase 2
BQYLC
Oníbodè gba iṣẹ-ṣiṣe ti aabo ayika
yoruba
female
18-29
phase 1
GSS7E
Rárá, wọn kò lọ sí ilé-ìwé lónìí
yoruba
female
18-29
phase 1
YP01K
Béèni o ma gbà waso.
yoruba
female
30-over
phase 1
QWSE1
Awọn olukọ ṣe awọn ọmọ ile-iwe ni awọn ibaraẹnisọrọ ti o nifẹ lati ṣe iwuri wọn
yoruba
female
18-29
phase 1
NGK6O
Kárọ̀tì dára fún ojú
yoruba
male
6-17
phase 1
EAE95
Ìdè kẹ̀kẹ́ naa bajẹ ni ọsẹ to kọja.
yoruba
male
18-29
phase 1
MZLHM
Obinna yóò ṣe akanṣe aṣa unifọmú mi ni ọla.
yoruba
male
18-29
phase 2
MWJC3
Akẹ́kọ̀ọ́ alábòójútó tí eré ìdárayá yóò ran àwọn akẹ́kọ̀ọ́ lọ́wọ́ nínú eré ìdárayá ilé sí ilé
yoruba
female
18-29
phase 1
MZLHM
Àwọn ènìyàn máa ń lò òkúta wẹ́wẹ́ àti irin láti fi gbé òpó ile ró.
yoruba
male
18-29
phase 2
XY1LS
Lọlá lọ sí sọ́ọ̀sì láti ṣeré
yoruba
male
30-over
phase 1
5O9PO
Àwọn jàndùkú hu ìwà ipá nínú ètò ìdìbò tó kọjá
yoruba
male
18-29
phase 1
O0GW8
Ipinlẹ̀ Ajike sàn bẹẹ̀lì fún awọn obìnrin tí o wà ní ẹ̀wọn.
yoruba
male
18-29
phase 2
7GZIN
Àwọn tí wọ́n yan ẹ̀yà irun ti kò le rárá yan ẹ̀yà irun ìràwọ̀ méjì
yoruba
female
30-over
phase 1
HH0CR
Rárá, àwùjọ wa ko dára tó
yoruba
male
18-29
phase 2
2BY6W
Àwọn igi tí àgbẹ̀ gbìn fani mọ́ra
yoruba
female
18-29
phase 1
UYTD3
Ṣé o máa lọ ibi ìsọ'mọlórúkọ náà?
yoruba
male
18-29
phase 1
MGWAM
Àwọn ẹyẹ ìdì wà lára àwọn ẹyẹ tó tóbi jù
yoruba
female
18-29
phase 2
RUYB2
A ni obo aburu kan ni abule mi
yoruba
female
18-29
phase 1
1ZFDK
Ilé ọtí tó wà ní ìpínlẹ̀ Èkìtì pọ̀.
yoruba
female
18-29
phase 1
7TZW9
Kúrò ní Ìkọ́ni ayélujára Snapchat.
yoruba
male
18-29
phase 2
2WJTR
Tọ́kọtaya máa ń fún ara wọ́n ní òrùka lọ́jọ́ ìgbéyàwó.
yoruba
female
18-29
phase 2
VRO6D
Ṣe iwọ yóò lo si politẹkínikì náa ni ọdun ti n bọ?
yoruba
female
18-29
phase 1
II8KP
Bọlá máa mú katakata wá sí inú oko ni ọ̀la
yoruba
female
18-29
phase 2
2OU1D
a sí má rí ẹyà nodulu títún sí ní Nàìjíríà.
yoruba
male
18-29
phase 1
7RVRP
Ọmọdébìnrin náà máa ṣe oúnjẹ alẹ́ fún gbogbo ènìyàn nínú ilé.
yoruba
male
18-29
phase 1
7R76Z
Bẹẹni, o ni ọkọ ayọkẹlẹ kan.
yoruba
female
30-over
phase 1
H1IP6
Gèlè wíwé máa di iṣẹ́ tọ̀kúnrin lọ́jọ́ iwájú
yoruba
female
30-over
phase 1
YH50Q
Ẹgúngún ni mò ń bọ̀.
yoruba
male
30-over
phase 1
59INZ
Ọkọ̀ òfurufú overland yóò gbéra lọ sí Ìpínlẹ̀ Oǹdó ni aago mẹ́wàá ààbọ̀ ní aárọ̀ ọla
yoruba
male
18-29
phase 2
MF6K9
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn yóò fẹ́ràn jíjẹ eso si ní ọjọ́ iwájú
yoruba
female
30-over
phase 1
LA0Y9
Kò sí ẹranko tó lè bá ọ̀bọ se ìdíje lórí igi
yoruba
female
18-29
phase 2
SJ7HS
Olú ẹ̀dá ìtàn ni mí
yoruba
female
30-over
phase 1
V6MKF
Àwọn òyìnbó amúnisìn ni wọ́n kọ́kọ́ mú èso apple wọ north America ní 17th century
yoruba
female
18-29
phase 2
IJ4DB
njé ibanilẹru lè fà irẹwẹsi?
yoruba
female
18-29
phase 1
4XT0F
àwọn orin ti wón kò ní ede Yoruba tí ń dì gbajúmò Orin.
yoruba
female
18-29
phase 2
7TZW9
Ìgbà tí mo pé ọmọ ọdún méjì-dínlógún ni mo kọ́ ọkọ̀ wíwà.
yoruba
male
18-29
phase 2
V6MKF
Òróró ólífì yóò ṣàn lórí sàláádì
yoruba
female
18-29
phase 2
43FB0
béèni, Èmi yóò mú kilasi ikẹkọ lórí instagram
yoruba
female
30-over
phase 2
SRYA7
Ìyàwó ilé pọ́nńbélé ni Ṣadé ń ṣe
yoruba
female
18-29
phase 2
UQD8C
Mo dá aṣọ mi láró ní ọ̀sẹ̀ tí ó kọjá
yoruba
female
18-29
phase 1
I1W1C
Bẹẹ̀lì jẹ ètọ̀ tí ófìn ti n gbà olújẹjọ láààyè láti tù sí ilẹ̀ latí àtímọ̀lẹ̀ ni isùnmọ̀tọ̀sì ìwàdìí, nígbàgbọ́gbọ́ pẹ̀lú àwọn ìpọ̀ kàn
yoruba
male
18-29
phase 1
J0OMN
Wọn tí ń gbèrò láti fi kún owó orí àwọn ilé ìfọwọ́pamo.
yoruba
female
6-17
phase 1
SJXWQ
Mo máa se núdùsì ní ọlá
yoruba
female
6-17
phase 1
4RO3C
Àwọn ajínígbé tí jí èèyàn bìí Èjìléníokòóléníẹ̀ẹ́dẹ́gbẹjo.
yoruba
female
18-29
phase 1
3D9SN
Imọ-ẹrọ yoo wa pẹlu pẹpẹ kikọ adaṣe
yoruba
female
30-over
phase 1
0C4JJ
Nọ́ọ̀sì Ade yóò darapọ̀ mọ́ ilé ìwòsàn
yoruba
female
18-29
phase 1
OVFI5
Ó lọ ṣọ́ọ̀ṣì lánàá
yoruba
female
18-29
phase 2
TL7W5
Ògòǹgò l'Ọba ẹyẹ.
yoruba
male
30-over
phase 1
2SCF8
Ọ̀rẹ́kùnrin mi jẹ́ ọkùnrin
yoruba
female
18-29
phase 2
84NFR
Pípa ẹja ti bẹ̀rẹ̀ láti bíi ẹgbẹ̀rún ọdún sẹ́yìn
yoruba
male
30-over
phase 1
TR90J
Táyọ̀ máa kọ bí wọ́n tí ń lùlù
yoruba
female
18-29
phase 1
5X30V
A rìn ìrin àjò lọ sí ìlú mí ní gbogbo oṣù to parí ọdún.
yoruba
female
30-over
phase 1
HNC7R
Bẹ́ẹ̀ni, mo ní ìfẹ́ àlọ àpamọ̀ gidi gan-an
yoruba
male
30-over
phase 1
IDEEJ
Ọkọ mi ò gbé ọkọ̀ ayọ́kẹ́lẹ́ rẹ̀ wálé nítorí nǹkan ń ṣe ìjánu rẹ̀
yoruba
female
30-over
phase 1
M9WPA
Oge gangan ni kí ènìyàn múra dáadáa
yoruba
female
6-17
phase 1
DHWIH
Data ni WhatsApp fi ń ṣiṣẹ́.
yoruba
male
30-over
phase 1
T0W7N
Ṣé yóò darapọ̀ mọ ẹgbẹ wa?
yoruba
female
30-over
phase 1
ERKIJ
Ǹjẹ́ ẹgbẹ́ àwọn ọkùnrin ìlú ṣe ìpàdé wọn lánàá ní ìgbàgede ìlú?
yoruba
male
30-over
phase 1
KSYPO
Wá gúnyán!
yoruba
female
18-29
phase 2
6UQ9S
Mà gbin àwọn irúgbìn oníkóró ní ìgbẹ̀yìn oṣù yìí.
yoruba
female
6-17
phase 1
End of preview. Expand in Data Studio
README.md exists but content is empty.
Downloads last month
2