audio audioduration (s) 0.06 34.8 | speaker_id stringlengths 5 5 | text stringlengths 9 180 | language stringclasses 1
value | gender stringclasses 2
values | age_range stringclasses 3
values | phase stringclasses 2
values |
|---|---|---|---|---|---|---|
Q7FW1 | Owó ẹyọ kan mélòó ló wà nínú ìkòkò ? | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
AAFBW | Olórí àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ọkùnrin àti obìnrin ni wón ń ṣiṣẹ́ adarí ní ilé ẹ̀kọ́ | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
O0GW8 | Ṣé Ọ̀gá ilé-ìwé nìyí? | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
AYSDG | Àwọn ohun àdáyébá ló ń ṣe àgbékalẹ̀ ètò ọrọ̀ ajé orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
MYLYJ | olùdarí ilé ìwé gígá yóò lọ si ibi ayẹyẹ ipari ẹkọ | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
HPTGN | Láyé òde òní, yàrá kọ̀ọ̀kan ló ń ní ilé ìwẹ̀ tirẹ̀ | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
VPQ8G | Ìdílé yẹn n lọ sí ọgbà iṣere àṣà ní ọjọ Kérésìmesì | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
KYBY1 | Àwọn ilé-ìfowópamọ́ ṣọ pé ẹ̀rọ afúnilówó máa ń ṣiṣẹ́ fún wákàtí mẹ́rìnlélógún. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
HNSNF | Ìjọ náà yóò sèwáàdí ìmọ̀ ẹ̀kọ́ bíbélì pásítọ̀ náà | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
OVFI5 | Ẹ̀pà àti fúláwà wàní ara èròǹjà ṣíṣe pínọtì. | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
J1RGK | Awakọ̀ náà kọ̀ látì san owó ọ̀nà ní ibùdó ọkọ̀ | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
ZHR4X | Mo máa wẹ ajá mi ní ọ̀la | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
W8MQ2 | Ọkùnrin náà yóò kùnà nítorí àìní ìbọ̀wọ̀ rẹ̀. | yoruba | female | 30-over | phase 2 | |
YT0T2 | Amharic ti nireti lati duro ede pataki ni Etiopia | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
IF56O | Táló ló kòmpútá yi nijètá? | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
7LN7A | Ẹgbẹ́ olóúnjẹ máa lo kílìṣìí fún ayẹyẹ náà | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
1OK1H | Ó ní láti kojú ìjìyà fún olè jíjà | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
KY5I7 | Ọsàn ní ohùn èlò pàtàkì. | yoruba | female | 30-over | phase 2 | |
03GAR | olùrànlówó olórí ilé ìwé ní ràn olórí ilé ìwé lọwọ. | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
ZLOOP | Fọlá yóò pade àwọn ọmọbìnrin náà lónìí! | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
5Q38Q | A máa wọ ọkọ òfurufú ní pápá òfurufú ẹ̀kọ́ lọ́la. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
2SCF8 | À̀wọn ọmọ mi fẹ́ràn bàbá wọn. | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
F2B3W | Rárá, ọba ni nígbàtí ó wà láyé. | yoruba | female | 6-17 | phase 1 | |
HH0CR | Olùbágbé wá kì ń bá èèyàn sọ̀rọ̀ | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
2WJTR | Òyà Irun àti ìparun jẹ́ àwọn ohun èlò ìserun pàtàkì | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
LRMKP | Ajá kì í gbàgbé olóore òwúrọ̀. | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
H7SAG | Àti òri Júmíyà ni mò ti rà Ibùsún ọ́mọ̀dẹ | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
IF56O | Tàyá mèrin ni òkò àkéró má n ni | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
MZLHM | Ẹn, Tolu ti gbé ilé-ajá rẹ̀ dé. | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
80W5Y | Mi ò rí aṣọ mi nínú aṣọ ẹrú mi | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
PNUGF | Pe olùtọ́jú Ilé-ìgbọ̀nsẹ̀ fún mi! Ọkùnrin náà pariwo | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
0UVE1 | Bíí ìlú ní yunifásítì ṣe rí. | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
NQAOZ | Iye olùgbé èèrà jẹ́ Ẹgbẹ̀rún kan àti ẹgbẹ̀rin ó lé ní àádọ́ta dín ní márùn-ún. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
7TZW9 | Aláńgbàá jẹ́ ẹranko ti a máa ń rí káàkiri. | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
YT0T2 | Títù lójú ni ìwà fífi ẹ̀bùn tàbí ìrúbọ fún àwọn òrìṣà tàbí ẹ̀mí. | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
YQUQL | Ṣé igi nìkan ni Ikan máa ń jẹ? | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
V6MKF | Ó sọ pé, 'Se cherie núdùsì' | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
31QDZ | Àwọn obìnrin ni ó máa ń sábà jẹ adelé ọba ní ilẹ Yorùbá | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
9B30E | Yorùbá gbàgbọ́ pé ọmọ tuntun jẹ́ àlejò ayé | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
Q6KV2 | Fi ámà yọ ìṣó yẹn | yoruba | female | 30-over | phase 2 | |
755YF | Eewọ lé já sí àbájáde ti òfin tí o ba ṣẹ | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
103WT | Ọlámilékan kì yóò sí ní ìpàdé tí yóò wáyé ní inú ọ́físì náà | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
LA0Y9 | Onirun yóò se irún iya mi lọla. | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
4GHNH | Láti ìgbà tí ìjọba ológun tí wọlé, wọ́n ti fagilé ẹ̀tọ́ ọmọnìyàn. | yoruba | female | 6-17 | phase 1 | |
LOISH | Olùkọ́-agba náà gbé bọọdi funfun kan wá sí kíláàsì mi lánàá. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
2BSPI | Mo wípé kí o mú ofarọ́ọ̀lù wa nísìsiyìí | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
304MQ | Téèpù ǹkan ni ohun tí wọ́n fi n wọn bí ǹkan ṣe jìnà tó àbí ìwọn nǹkan | yoruba | female | 6-17 | phase 1 | |
2SCF8 | Ti àwọn géétì ẹ̀wọ̀n! | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
OVFI5 | Irun àti ṣíṣe ojú lọ́ge ń gbà ènìyàn láàyè lati gbìyànjú àwọn ìwò oriṣiriṣi | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
FS6M9 | Tábìlì iṣẹ́ tí bàjé. | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
417S4 | Láàbù kẹ́mísítírì ni wọ́n ti máà ń sáábà rí àwọn kẹ́míkà | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
P8MHS | Ṣe o le ṣi akọọlẹ naa lana? | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
TMNER | Béèni ègbé òṣèlú yén tí yàn ti ẹní tí o má aṣojú wón. | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
ZLJPP | Àwọn ọmọ ológun America n ran àwọn omo ológun Ukraine lọ́wọ́ | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
GZ44W | Baba rẹ jẹ olukọ ere idaraya nigbati o wa laaye | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
TOZM7 | Ní oṣù keje ọdún yìí, àwọn ẹgbẹ ọmọ ogun kan ní Niger fí ipá gba ìjọba. | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
I8WRZ | Jig saw náà kan sì meji | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
HZM4L | Àwọn ọ̀dọ́ ó le ni ifẹ sì kíkọ́ ọ̀nà láti máa ṣe àgbo Ìbílẹ̀ | yoruba | female | 30-over | phase 2 | |
SDW28 | Adébáyọ̀ ra Pọfupọ́ọ̀fù ní àná | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
M8U45 | Ìyá àgbà ń pa Àlọ́ fún àwọn ọmọdé | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
MXTT9 | Ní àtijọ́, àwọn ènìyàn kọ̀ọ̀kan dojú kọ ìbáṣepọ̀ tí kò dára bí ìgbẹ́kẹ̀lé ṣe bàjẹ́ nígbà tí irọ́ wọn farahàn. | yoruba | male | 30-over | phase 2 | |
59INZ | Tọ́lá ní àádọ́jọ náírà lọ́wọ́ | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
VH6DZ | Bisi ra jollof rice ni ilé oúnjẹ ken. | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
CSLLW | Ẹyin ẹni tó bá ṣòtítọ́ ni mo wà | yoruba | male | 6-17 | phase 1 | |
3L2UX | Dọlápọ̀ tọ́jú àpò ìrajà rẹ pamọ́ fún mi | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
ELC7E | Ta ni ó lo gege yìí? | yoruba | male | 30-over | phase 2 | |
OZCG2 | Ilé ì̀wòsàn kò wọ́pọ̀ ní àwùjọ Yorùbá ní ayé àtijọ́ | yoruba | female | 30-over | phase 2 | |
HSOVJ | Asojúlóge kò tètè dé sí ibùdó ìyaeré. | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
8SU86 | ṣé ó ṣàgbèrè? | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
24ZOQ | Ó yọ ẹ̀wọ̀n kẹ̀kẹ́ náà. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
RGSKP | Kas̩íá tí Bó̩lá bá lórí ìjókòó s̩àlàyé bí yóò s̩e buwó̩ lu fó̩ò̩mù náà | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
ZLOOP | Ṣé ọ̀nà ìfijíṣẹ́ kó ipa pàtàkì nínú ayẹyẹ Ìmúw'ẹgbẹ́ ? | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
ZOL9F | Àwọn ageri miran ló atike Onigerun | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
KZZZO | Tíátà àti fíìmù jé̩ ò̩kan lára ò̩nà ìdárayá àti è̩kó̩ ní àwùjo̩ | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
E9NLH | Mo ti pa aláǹtakùn yẹn kí o tó sọ̀rọ̀ | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
CSMDP | Mo gbọ́ tí bàbá mi pariwo mọ́ awakọ̀ wọn ní ọjọ́ Àìkú pé "gbówó mi wá!" | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
PET7A | Bàbá ìyàwó mi kú ní oṣù díẹ̀ sẹ́yìn. | yoruba | male | 6-17 | phase 1 | |
IF56O | Áwòn ónijibiti yèn á fi ójú bá ilé èjò lòsè tó n bò | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
VAO6L | Aṣọ ẹgbẹ́-jọdá wo ni o wọ̀ ní àná? | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
VAO6L | Ṣé yóò lè ríran lẹ́yìn iṣẹ́ abẹ | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
CGQWW | Pápá ọkọ ofurufu n ṣe ifilọlẹ ebute tuntun loni. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
2PK17 | ATM ni a ma lo fun awọn iṣowo owo | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
H68JS | Àwọn akọrin náà wọ aṣọ funfun ài dúdú. | yoruba | male | 6-17 | phase 1 | |
LRMKP | Adájọ́ ni ó máa ń darí ní ilé-ẹjọ́. | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
OZCG2 | Lọ sí ilé onídìrí báyìí! | yoruba | female | 30-over | phase 2 | |
JJU4N | Obìnrin náà ní kókó ní inú ọmú rẹ | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
MXTT9 | Ohun adarí mọ́tò yìí kì í ṣe tiwa. | yoruba | male | 30-over | phase 2 | |
MZLHM | Rárá, mi ò kí ń ja ìjàkadì. | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
GC0LB | Àwọn ọmọkùnrin náà yóò wá ìyọ̀ṣó tó sọnù. | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
NHXYV | Ìyá mi pa adìẹ fún Easter. | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
8YN0Q | Ẹnu ìyá mi ni mo ti gbọ́ ìtàn ìfẹ́ Romeo and Juliet | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
FWM6P | Ọ̀rọ̀ òye máa mú ọlọ́kàn gíga tẹríba. | yoruba | female | 6-17 | phase 1 | |
MZLHM | Àwọn ènìyàn máa ń dáṣà oríṣiríṣi ọ̀rọ̀ nínú gẹ́tò. | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
IUWY6 | Akápò ilé ìwé yóò pèsè ìwé-ọjà fún àwọn akẹ́kọ̀ọ́ lẹ́yìn tí wọ́n bá san owó ilé ìwé | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
8C1U5 | Orí ewúré dára láti fi se pepper soup | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
8NTXE | Fúnkẹ́ yóò wà ní ilé ìseré orí-ìtágé ní dédé aago mẹ́ẹ́fà | yoruba | male | 6-17 | phase 1 | |
HIZA4 | Òògùn àtọgbẹ ti mo ta fún àwọn oníbàárà wa ti tan lọ́sẹ̀ tó kọjá. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
K4GZK | Táni ádári gbógbó gáráji Ékó? | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
JVDL9 | Ọmọbìnrin mi kò lè pé ogún náírà. | yoruba | male | 6-17 | phase 1 | |
KIIB6 | Rárá, kò sí àlàyé nípa Bolarinwa tí ó ń ṣètò irú ìgbéyàwó bẹ́ẹ̀. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 |
End of preview. Expand in Data Studio
README.md exists but content is empty.
- Downloads last month
- 7