audio
audioduration (s) 0.06
24.4
| speaker_id
stringlengths 5
5
| text
stringlengths 7
193
| language
stringclasses 1
value | gender
stringclasses 2
values | age_range
stringclasses 3
values | phase
stringclasses 2
values |
|---|---|---|---|---|---|---|
HZAHG
|
Tolani ni ámọ̀kókó tò ṣé ikòkò yi
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 1
|
|
KSYPO
|
Àwọn ìwé pélébé dára fún ìpèsáyẹyẹ.
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 2
|
|
JR5WW
|
Ta ló ń wo tẹlifisan ninu yàrá?
|
yoruba
|
male
|
30-over
|
phase 1
|
|
H32AC
|
Oṣù Méjì sẹ́yìn ni ìkókó náà pé ọdún kan
|
yoruba
|
female
|
30-over
|
phase 1
|
|
XNYAV
|
Agbẹjọ́rò náà wípé, "Má jẹ́ kí ọ̀rọ̀ kan jáde ní ẹnu rẹ!"
|
yoruba
|
female
|
30-over
|
phase 1
|
|
MXSBU
|
Awọn ìsò onigbajamo ní a lọ bí àwọn ile-iṣẹ́ wíwò láti wó bọọlu
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 1
|
|
OVFI5
|
Garri sì máa di oúnjẹ gbogbogboo
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 2
|
|
Q54MY
|
Ní ọjọ́ iwájú, wọn yóò gba àwọn ènìyàn tí ó ní àìsàn ọgbẹ́ inú ní ìyànjú láti dẹkùn wàhálà ṣíṣe
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 2
|
|
YT0T2
|
Olórin fújì ni Àlàbí Pasuma.
|
yoruba
|
male
|
18-29
|
phase 2
|
|
DBKQL
|
Ṣé a sì máa ra èyí ní ẹgbẹ̀wáléní ọgọ́san?
|
yoruba
|
male
|
18-29
|
phase 1
|
|
HZM4L
|
Bẹ́ẹ̀ ni, olùkọ́ wa kọ́ wa ní ọ̀sẹ̀ tó kọjá.
|
yoruba
|
female
|
30-over
|
phase 2
|
|
3CDW5
|
Awọn ọrẹ pẹlu awọn eto anfani wa ṣugbọn wọn ko ni ijiroro ni gbangba
|
yoruba
|
female
|
6-17
|
phase 1
|
|
IDEEJ
|
Bàbáa bàbá mi ni àgbà tára rè jípépé jùlọ lábúlé
|
yoruba
|
female
|
30-over
|
phase 1
|
|
R5ILL
|
Ìkóniláyàjé̩ lórí è̩ro̩ ayélujára wó̩pò̩ láàárín àwo̩n ò̩dó̩ pàápàá àwo̩n o̩mo̩ ilé ìwé
|
yoruba
|
male
|
18-29
|
phase 1
|
|
GBTGX
|
Inú bí alága ẹgbẹ́ àwọn oníṣòwò tí abàa Súlè lànà si àwọn ọmọ ẹgbẹ́.
|
yoruba
|
female
|
6-17
|
phase 1
|
|
O0GW8
|
Mà á lọ pọ́n ọ̀bẹ yẹn lọ́la
|
yoruba
|
male
|
18-29
|
phase 2
|
|
JG8DC
|
Nígbà tí a lọ fún ayẹyẹ ọ̀uń, ilé ìgbàlejò tí a sùn sí kò ní òdò omi iwẹ̀.
|
yoruba
|
male
|
18-29
|
phase 1
|
|
MGWAM
|
Rárá, Nọọ̀ṣì Tóbi kò wọ̀ àṣọ̀ rẹ̀ lánà.
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 2
|
|
D10NS
|
Ìṣojúlóge ní ọjọ́ iwájú yóò yatọ̀ sí ti àtijọ́
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 1
|
|
NUP61
|
Oru wà nínú yàrá mi.
|
yoruba
|
female
|
30-over
|
phase 1
|
|
4XT0F
|
Gbá òdodo náà!
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 2
|
|
L88Q7
|
Àlọ́ àpamọ dàbí àdìtú.
|
yoruba
|
female
|
30-over
|
phase 1
|
|
JS59W
|
A mà hún ló Sọfẹli ni ìlẹ́ kọsíròsìọnú làtí pó símẹtí
|
yoruba
|
female
|
30-over
|
phase 1
|
|
8Y12V
|
Segun yóò tá igbó fún ọrẹ rẹ ní ọ̀la
|
yoruba
|
male
|
18-29
|
phase 1
|
|
YT0T2
|
Pè obìnrin yẹn fún mi
|
yoruba
|
male
|
18-29
|
phase 2
|
|
2WJTR
|
Arákùnrin tí ó lọ sí gbàgede tí wọ́n tí ń gbá bọ́ọ̀lù ní àná náà tí dé bí
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 2
|
|
M1DRD
|
Mo máa jáde pẹ̀lú rẹ ní ọjọ́ ẹtì
|
yoruba
|
female
|
6-17
|
phase 1
|
|
KY5I7
|
Tínko tínko jẹ́ eré tí a máa ń ṣe.
|
yoruba
|
female
|
30-over
|
phase 2
|
|
43FB0
|
Kílódé tí wọ́n fi pariwo ní yàrá ìgbẹ́jọ́ lánàá?
|
yoruba
|
female
|
30-over
|
phase 2
|
|
Q54MY
|
Ṣé ìyá yín wà ní ilé?
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 2
|
|
HPTGN
|
A lọ sí ibi ayẹyẹ ikomojade lánàá
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 2
|
|
9MWSV
|
Mo máa lọ sí ibùdó omi náà láti gbádùn ara mi.
|
yoruba
|
female
|
30-over
|
phase 1
|
|
FAGZG
|
Igbẹmi ara ẹni jẹ ọkan ninu awọn iru iku ni awujọ ode oni
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 1
|
|
ZHR4X
|
Mo máa ra ìwọ̀n mìíràn ni ọ̀la
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 2
|
|
V77RP
|
Ilé àwọn adẹ́tẹ̀ ń ran àwọn èèyàn tó dẹ́tẹ̀ lọ́wọ́
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 1
|
|
R5PXE
|
A máa ṣeré aláyò ni gbọ̀ngàn ìgbafẹ́ náà ni ọ̀la
|
yoruba
|
male
|
18-29
|
phase 1
|
|
6NJCQ
|
Arakunrin mi yoo ra aso ti owo egberun lona mejila o le mokandinlogoji dọla ni ọla
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 1
|
|
96ZKW
|
Iye asọ re jẹ aadọta naira.
|
yoruba
|
male
|
18-29
|
phase 1
|
|
EN10J
|
Idije tẹníìsì yoo wa ni ọla ni ìle-ìwe mi.
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 1
|
|
NHXYV
|
Rárá, èmi yóò rìn ìrin àjò lórí títì.
|
yoruba
|
female
|
30-over
|
phase 1
|
|
ZLOOP
|
Njẹ olórí ijọba kópa ninu awọn ayẹyẹ náà?
|
yoruba
|
male
|
18-29
|
phase 2
|
|
AGDH6
|
Bẹ́ẹ̀ni,Àga èèyàn èjì dín ní ẹgbàá ní mo fẹ́ lọ kó ni àná .
|
yoruba
|
male
|
30-over
|
phase 1
|
|
KY5I7
|
Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ wa yóò jáwé olùborí níbi ìtakùrọ̀sọ láàrin ilé-ìwé sí ilé-ìwé náà
|
yoruba
|
female
|
30-over
|
phase 2
|
|
HL8TT
|
Àgbọn ni mò ń tà.
|
yoruba
|
female
|
30-over
|
phase 1
|
|
8HDWA
|
Billy bẹ̀rẹ̀ Ìpátá nígbà tí ìyà rẹ̀ kọ̀ láti ra ohun ìṣeré akérò fún un.
|
yoruba
|
male
|
18-29
|
phase 1
|
|
KWHRH
|
Bẹ́ẹ̀ni, fámásìst ni.
|
yoruba
|
female
|
30-over
|
phase 1
|
|
VAO6L
|
Ọba ní kí ẹ wá gba àwọn ìlù mìíràn ní ọdún tó n bọ
|
yoruba
|
male
|
18-29
|
phase 2
|
|
UN3LQ
|
Pín ọtí panipani "Goldberg" ni ọ̀la.
|
yoruba
|
male
|
18-29
|
phase 1
|
|
IF56O
|
Nibó ló wá ni Mushin nijètá?
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 2
|
|
CSMDP
|
Irọ́ ni pé ìyá ìyá rẹ̀ lé ní èjì-lé-ní-irínwó ọdún.
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 2
|
|
MXTT9
|
Ọmọ náà ń mú ọmú ìyá rẹ̀.
|
yoruba
|
male
|
30-over
|
phase 2
|
|
TB888
|
Tomiwa sọ pe oun yoo kọ ile ijọsin fun baba rẹ
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 1
|
|
E69XO
|
Báwo ni ọkọ̀ ọjọ́ iwájú ṣe lè fojúsùn
|
yoruba
|
male
|
18-29
|
phase 1
|
|
GCSGN
|
Bẹ́ẹ̀ni, “ewé ìbẹ́pẹ” yóò wúlò.
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 1
|
|
KSYPO
|
Nígbà tí o fi sórí tábìlì ọ̀gá ni wọ́n mu.
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 2
|
|
MYLYJ
|
Akọ̀we ni ó máa ń ṣàkóso àkọsílẹ̀ nípa àwọn akẹ́kọ̀ọ́ nínú ilé ìwé fáfitì
|
yoruba
|
female
|
30-over
|
phase 1
|
|
ZLOOP
|
Ǹjẹ́ àwọn ènìyàn máa ń lo isẹ́ ọnà àti iṣẹ́ ọwọ́ láti ṣàlàyé ohun àtinúdá àti àṣà ìdánimọ̀ wọn?
|
yoruba
|
male
|
18-29
|
phase 2
|
|
GTI5O
|
Ìjoba àpapò Nàìjíríà yóò fún ilé isé epo ròbì ní ójìlélé̩gbè̩fà mílíó̩nù náírà ni o̩dún tó n bò̩
|
yoruba
|
male
|
18-29
|
phase 1
|
|
VAO6L
|
Mu iho wa nibi
|
yoruba
|
male
|
18-29
|
phase 2
|
|
C6D2E
|
Dókítà náà sọ wípé iṣẹ abẹ náà o ní mú ìrora dànù.
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 1
|
|
N1PAK
|
Lọ́ládé yóò ta àwọn bàtà rẹ̀ ní ibi pápá ìseré náà ní ọjọ́ àìkú
|
yoruba
|
male
|
30-over
|
phase 1
|
|
IOHG4
|
Òpó iná ni àwọn òṣìṣẹ́ iná ilé iṣẹ́ iná ti ń jáná.
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 1
|
|
XAVV1
|
Kérésìmesì ni àjọyọ̀ ọjọ́ ìbí Jésù.
|
yoruba
|
male
|
18-29
|
phase 1
|
|
SWZ18
|
Ṣé wa tún mótò tuntun rẹ ṣe?
|
yoruba
|
female
|
30-over
|
phase 1
|
|
EUJPT
|
Bẹ́ẹ̀ni màá kun irun mi sí dúdú
|
yoruba
|
female
|
6-17
|
phase 1
|
|
FWJFI
|
Ṣíbí pọ̀ nínú ilé wa.
|
yoruba
|
male
|
30-over
|
phase 1
|
|
QF5AT
|
Oríṣiríṣi ẹka ni ó ma ń ní.
|
yoruba
|
male
|
30-over
|
phase 1
|
|
GHD08
|
Máà kó oúnjẹ lọ sí ilé aláìníìyá lọ́sẹ̀ yìí
|
yoruba
|
male
|
30-over
|
phase 1
|
|
FBKHQ
|
Àwọn Mùsùlùmí ma bọ bàtà wọn kí wọ́n tó wọ mọ́sálásí.
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 1
|
|
HH0CR
|
Ẹ dọ̀bálẹ̀ kí Ọba!
|
yoruba
|
male
|
18-29
|
phase 2
|
|
N4O1M
|
Màá ṣe ọdún kérésìmesì ní osù tó ń bọ̀ pẹ̀lú àwọn ẹbí mi
|
yoruba
|
female
|
30-over
|
phase 1
|
|
TB888
|
Awọn ayaworan ile yoo fa awọn ile ti awọn bungalow
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 1
|
|
Y5W7U
|
Inú igbó ńlá ni ẹranko ègàn máa ń gbé.
|
yoruba
|
female
|
6-17
|
phase 1
|
|
884H4
|
Mo má ń dá irun mi sí nígbà kan
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 1
|
|
4YIRH
|
Olú se màkàrónì lójujúmọ́
|
yoruba
|
male
|
18-29
|
phase 1
|
|
UYTD3
|
ṣé wọn yóò si lo òǹkà owó-ẹyọ?
|
yoruba
|
male
|
18-29
|
phase 1
|
|
ZO98Y
|
A máa kórè lọ́la kí a le dí ọgbàrà lọ́wọ́ láti má fọ àwọn irúgbìn lọ.
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 1
|
|
KSYPO
|
O ní àǹfààní láti mú ẹlẹ́rìí rẹ wá sí ilé ẹjọ́
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 2
|
|
4XT0F
|
Ilé óúnjẹ máa má pọ̀ si.
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 2
|
|
YT0T2
|
Kílásì jẹ́ agbègbè tó rọrùn fún ẹ̀kọ́
|
yoruba
|
male
|
18-29
|
phase 2
|
|
Q54MY
|
Ṣé ilé ọtí wà ní ilé ìtura náà?
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 2
|
|
G64SU
|
Dayọ̀ yóò bọ̀wọ̀ fún ìyá rẹ
|
yoruba
|
female
|
30-over
|
phase 1
|
|
44FJ6
|
Abimbola ni a máa fún ní Parasitamọ́ọ̀ náà
|
yoruba
|
male
|
30-over
|
phase 1
|
|
MYLYJ
|
Òjòlá náà kò lè gbé ajá náà mì.
|
yoruba
|
female
|
30-over
|
phase 1
|
|
WYG3R
|
Olú ìlú ni Àbújá jẹ́ fún orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.
|
yoruba
|
male
|
18-29
|
phase 1
|
|
M0FG7
|
Báwo ni obìnrin pẹ́lẹ́ńgẹ yìí ṣe ń lu ọkọ rẹ?
|
yoruba
|
male
|
18-29
|
phase 1
|
|
2JZTK
|
Ní yàrá ìdájọ́ àwọn agbẹjẹ́rọ̀ ṣe àgbékalẹ̀ ọranyan àríyànjiyàn wọn.
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 1
|
|
MM9FZ
|
Ogún ọdún ni wọ́n dájọ́ fún Tolu
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 1
|
|
8AC9O
|
Njé o tí dì Olórí ẹka ẹkọ?
|
yoruba
|
male
|
30-over
|
phase 1
|
|
OYBT6
|
Ọ gbọdọ̀ gbà ìgbànlíààyè láti ọdọ̀ ènì pátákì ní ohùn tí aláḳọ̀sọ̀ mi sọ̀ fun mi lànà.
|
yoruba
|
male
|
18-29
|
phase 1
|
|
38XYG
|
A ó lọ kí Kíkẹ́ pé ókú ilédè nígbàtí ìyá rẹ̀ bá rìn ìrìn àjò lọ
|
yoruba
|
female
|
6-17
|
phase 1
|
|
SK7NA
|
Mo san ẹgbẹ̀rún márùn-ún fún owó ọkọ̀ nígbà tí mò ń rìnrìn àjò ní ọ̀sẹ̀ tí ó kọjá
|
yoruba
|
male
|
6-17
|
phase 1
|
|
SEDW4
|
Yorùbá a kí onídìrí pé ojú gboro o.
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 1
|
|
SJZWL
|
Tosin ló ibúprófini nitóri àrá riró nijẹ̀tá
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 1
|
|
L88Q7
|
Ilé-ìwé gbúdọ̀ ni olùkọ̀-àgbà.
|
yoruba
|
male
|
30-over
|
phase 1
|
|
3N59Z
|
Pírífẹ̀tì yàrá-ìkàwé náà n to àwọn ìwé tó wà nínú yàrá ìkàwé
|
yoruba
|
male
|
18-29
|
phase 1
|
|
APQO2
|
Bẹ́ẹ̀ni, òun ló ń jẹ ewúro
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 1
|
|
HNSNF
|
Àwọn ọ̀daràn mẹ́wàá ni wọ́n pa ní ọ̀sẹ̀ tó kọjá.
|
yoruba
|
female
|
18-29
|
phase 2
|
|
HH0CR
|
Oṣuwọn alainiṣẹ ni Nigeria ga
|
yoruba
|
male
|
18-29
|
phase 2
|
|
RB8QQ
|
Ọjà maili méjìlá ni ọjà tó èso àti Ẹ̀fọ́ tó tóbi ní Ìpínlẹ̀ èkó.
|
yoruba
|
female
|
30-over
|
phase 1
|
End of preview. Expand
in Data Studio
README.md exists but content is empty.
- Downloads last month
- 1