Dataset Viewer
Auto-converted to Parquet Duplicate
audio
audioduration (s)
0.06
37.4
speaker_id
stringlengths
5
5
text
stringlengths
7
194
language
stringclasses
1 value
gender
stringclasses
2 values
age_range
stringclasses
3 values
phase
stringclasses
2 values
HNSNF
Atúnkọ̀se náà yóò tún ọkọ̀ ayọ́kẹ́lẹ́ náà ṣe kí ó tó dénú kọlẹ̀.
yoruba
female
18-29
phase 2
MXTT9
Bàbá mi wá láti Kano.
yoruba
male
30-over
phase 2
HH0CR
Nátì ń kọrin láti àárọ̀
yoruba
male
18-29
phase 2
HZM4L
Iṣẹ́ Agbẹ́gilére ni Adebola ń ṣe
yoruba
female
30-over
phase 2
3O6YU
Àwọn ológun yóò wọ únífọ́ọ́mù kakí wọn lọ sójú ogun.
yoruba
male
18-29
phase 1
ZHR4X
Báwo ni Folú yóò ṣe kí àwọn òbí rẹ̀ ní ọ̀sán?
yoruba
female
18-29
phase 2
L88Q7
Awakọ̀-òfurufú máa ń wa ọkọ̀ ofurufú.
yoruba
male
30-over
phase 1
QQQPJ
Wọn yóò pa Gómìnà náà ní ọ̀la
yoruba
female
30-over
phase 1
UYTD3
Ṣé ìpàdé àwọn oníjó máa wà ní ọjọ́ ẹtì?
yoruba
male
18-29
phase 1
YEI1F
Ọ̀pọ̀ àwọn èèyàn tí ṣọwọ́ nù sínú kírípítò, síbẹ̀ wọ́n n sí ṣòwò nínú rẹ̀
yoruba
male
18-29
phase 1
FEA5I
Aṣọ ẹgbẹ́ àwọn ológun yàtọ sí tí àwọn ọlọ́pàá
yoruba
female
18-29
phase 1
V6MKF
Ìbaráẹ̀nisọ̀rọ imọ̀lárà dábì fífírànṣẹ̀ àwọn ìfírànṣẹ̀ ìyàrá pẹ̀lú àwọn àwòrán àti àwọn fídíò sí àwọn ọ̀rẹ̀ ní lilo òhùn elo kàn tí à pé ní Snapchat.
yoruba
female
18-29
phase 2
WH65Z
Kẹ́míkàlì àti ohun èlò gbọ́dọ̀ wà ní yàrá ìmọ̀ kẹ̀mísírì
yoruba
female
18-29
phase 1
ZLOOP
Àlọ́ àpagbè máa ń gba kí èèyàn ó ní làákàyè kí ó tó lè dáhùn ìbéèrè
yoruba
male
18-29
phase 2
MGWAM
A yọ̀ọ̀ lọ sí ibùdó ọkọ ojú irin ni aṣálẹ̀
yoruba
female
18-29
phase 2
NNF2G
Marun wa laaye ati chivita jẹ awọn burandi oje olokiki.
yoruba
female
6-17
phase 1
AGXXX
GRA jẹ́ ọ̀rọ̀ tí a máa ń lò ní Èkó àti àwọn ẹ̀ka orílẹ̀-èdè Nàìjíríà mìíràn.
yoruba
female
6-17
phase 1
VAO6L
Díìnì ẹ̀ka ẹ̀kọ́ áàtì yóò bá àwọn olùkọ́ sọ̀rọ̀ ní ọ̀la.
yoruba
male
18-29
phase 2
8UOIO
Obìnrin náà sọ pé òun yóò gé irun rẹ̀ ní ọ̀la
yoruba
female
18-29
phase 1
AGXXX
Ọkọ̀ ojú omi ni ó máa ń ko àwọn ọjà wọ ori ilẹ̀ èdè yìí
yoruba
female
6-17
phase 1
V6MKF
Rárá, ó máa lò ó ní ọ̀sán
yoruba
female
18-29
phase 2
18HBU
Mó n gbé àpó irèsí this lò silé
yoruba
male
18-29
phase 1
9TU33
O léwu fún ọmọdé láti máa fí Ọ̀bọ̀ọ̀nbọọ̀n ṣeré.
yoruba
male
30-over
phase 1
IF56O
Siga le fa akàn ẹdọfóró
yoruba
female
18-29
phase 2
ELC7E
Ébùté wá ni Kàlábá
yoruba
male
30-over
phase 2
F1Y61
Irin náà ní ìwọ̀n àádọta kílò
yoruba
male
30-over
phase 1
CIWB3
Ṣọlá ń ra ọkọ̀ lọ́wọ́lọ́wọ́.
yoruba
female
18-29
phase 1
EGNSI
Ìgbà wo ni ẹ o ṣe ìgbéyàwó?
yoruba
female
18-29
phase 1
6ADHW
ọkò ìdòtí yóò wá gbé
yoruba
female
30-over
phase 1
MZLHM
Rárá, mi ò lọ sí ibi ìkómọ baba àgbà ní ọ̀sẹ̀ tó lọ.
yoruba
male
18-29
phase 2
Q6KV2
Kini awọn ojuse pataki ti akọle Otunba?
yoruba
female
30-over
phase 2
Q7FW1
Ilé alájà méjì ni mò ń gbé.
yoruba
female
18-29
phase 2
O0GW8
Mà á lọ wòó lóri Tiktok lọ́la
yoruba
male
18-29
phase 2
FE6OQ
Wọ́n ṣàlàyé aso ìgbábóòlù fún gbogbo ọmọ ẹgbẹ́ agbá bọ́ọ̀lù orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.
yoruba
female
30-over
phase 1
MGWAM
Ṣé ọ̀sẹ̀ tó ún bọ̀ ni ẹ máa lọ rí abánigbàyè ọkọ̀ ojú òfurufú??
yoruba
female
18-29
phase 2
NZ4Y3
Ọ̀rẹ́ mi ń ṣiṣẹ́ ní ilé ìfowópamọ́ fidẹ́lítì
yoruba
male
30-over
phase 1
ZLOOP
Ìkolà fun ọ́mọ́bìnrin je mi mu díẹ̀ tàbi gbogbo ẹ̀yà-ojú ara nkàn ọ́mọ́bìnrin kúrò .
yoruba
male
18-29
phase 2
9YYDN
Ibo ni ilé ẹgbẹ́ Labour wà ní ìpínlẹ̀ Èkó?
yoruba
female
18-29
phase 1
9B30E
Ẹ kú ará feraku ni Yoruba ń kí ẹni tí òkú kú fún
yoruba
female
30-over
phase 1
FWM6P
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn aláàbọ̀ ara ti fún àwọn ènìyàn ni èroàfiyé burúkú nípa ẹni tí wọ́n jẹ
yoruba
female
6-17
phase 1
M8U45
Ìyá àgbà ń ta Karosíìnù fún àwọn oníbàárà wọn níta
yoruba
female
30-over
phase 1
CSMDP
Nígbà náà báwo ni o ṣe mọ̀ pé oyún ṣíṣẹ́ le yọrí sí ikú?
yoruba
female
18-29
phase 2
JL8Y6
Èmi yóò fẹ́ràn láti ṣe audio call ní alẹ́ yìí.
yoruba
female
18-29
phase 1
59INZ
Ilé-ìtura ti Tráńskọ́pù lèyí tó tóbi jù lọ ní Nàìjíríà
yoruba
male
18-29
phase 2
HPTGN
Bàbá àgbà wa ti dé láti ìrìnàjò
yoruba
female
18-29
phase 2
RGGO9
Ọgbà Bọ́ọ̀lù alápẹ̀rẹ̀ gba àlejò eré ìdárayá àti àwọn iṣẹ́ ṣíṣe
yoruba
male
18-29
phase 1
MZLHM
Àwọn tí wọ́n bá ń sáré ni wọ́n ń pè ní eléré.
yoruba
male
18-29
phase 2
DEU78
On colos, on colos, jẹ́ èdè orí titi.
yoruba
male
18-29
phase 1
KSYPO
Inú gbogbo ará ìlú ń dùn pé a ti ní Ọba tuntun
yoruba
female
18-29
phase 2
KROKG
Bolaji já efinrin fún jẹ́dì-jẹ́dì rẹ̀
yoruba
female
30-over
phase 1
Q7FW1
Mo ní kí o fi ojú sí bí wọ́n se ń ko iná ní àgbẹ̀dẹ
yoruba
female
18-29
phase 2
VA7RM
Ilé-iṣẹ́ rédíò àkọ́kọ́ ní Nàìjíríà jẹ́ Ibùsọ̀ Ìgbóhùsáfẹ́fẹ́ Rédíò (RBS).
yoruba
male
18-29
phase 1
HZM4L
Bẹ́ẹ̀ni, àwọn yàrá méjì wà tó ṣófo nínú ilé ìgbé mi.
yoruba
female
30-over
phase 2
YN19E
Ó ní àwọn ọkùnrin kan tí ó kúndùn fífẹ́ ju obìnrin kan lọ.
yoruba
male
30-over
phase 1
VAO6L
Ó wà ní Yólà
yoruba
male
18-29
phase 2
5XYIB
Awọn idile le darapọ ni awọn aaye foju han gbangba
yoruba
male
30-over
phase 1
WSYC1
Àwo̩n abò̩gún yóò bè̩rè̩ o̩dún wo̩n ní ò̩la
yoruba
female
18-29
phase 1
MZLHM
Ẹ́ran ẹlẹdẹ jẹ̀ bí ọ̀unjẹ̀ ti a làárà awọn ẹlẹdẹ.
yoruba
male
18-29
phase 2
6ADHW
àwo àlẹ̀mọ́lẹ̀ yẹn rẹwà
yoruba
female
30-over
phase 1
U8CG7
New York jẹ́ ìlú tí ó wà ní orílẹ̀-èdè United States of America.
yoruba
female
18-29
phase 1
LYE5W
Akin fi ìlú ẹ̀lẹ́yàmẹ́yà náà sílẹ̀.
yoruba
male
30-over
phase 1
OZCG2
Tẹ́lẹ̀ àwọn ìtọ́sọ́nà fún wíwọ àwọn aṣọ ológun nígbà iṣẹ́ rẹ
yoruba
female
30-over
phase 2
ZJ3AR
Ọ̀rẹ́ mi tí ó máa ń bá ènìyàn gba'lé ní ó dára ki ẹni tó lọmọ gba ilé òní-filáátì mẹ́ta.
yoruba
female
18-29
phase 1
FTDAG
Òrùka ìgbéyàwó ní ìtumọ̀.
yoruba
female
18-29
phase 1
A64XD
Rárá, ó fún un ní fáànù kékeré
yoruba
male
6-17
phase 1
MZLHM
Àwọn ènìyàn máa ń nifẹ si oúnjẹ ókéré ju tilẹ̀ wá lọ
yoruba
male
18-29
phase 2
VAO6L
Gbógbó wón n'reti ibusùn nlá
yoruba
male
18-29
phase 2
CCDO7
Ǹjé̩ ìwó̩ náà le lo òkúta ìfò̩sè̩ nínú balùwè̩ ló̩jó̩ iwájú?
yoruba
female
18-29
phase 1
OVFI5
Lọ sí ọ̀dọ̀ olúawo ni ọ̀túnla!
yoruba
female
18-29
phase 2
W8MQ2
Arákùnrin náà kọ́ ilé olókè meji
yoruba
female
30-over
phase 2
1ERA7
Olùdarí ibùdókọ̀-ojú-omi ti mojútó gbogbo iṣẹ́ òní
yoruba
male
30-over
phase 1
M8U45
Ìyá àgbà tọ́ ewédú wọn kán tó sèé .
yoruba
female
30-over
phase 1
JDOLK
Kòkòrò náà yóò ṣe ikú Pání ti ko ba tọju
yoruba
female
18-29
phase 1
JG0TY
Wọ́n ní kí wọ́n ṣe ṣùkú ní iléèwé ni ọ̀sẹ̀ tó kọjá
yoruba
female
18-29
phase 1
CZ18P
Mo wa ninu odò-àtọwọ́dá nígbàtí o n pe ni alẹ́ àná.
yoruba
male
18-29
phase 1
MXTT9
Gáásì ni ọ̀pọ̀lọpọ̀ ilé ní Nàìjíríà fi ń dáná.
yoruba
male
30-over
phase 2
Q54MY
Indomie dara lati jẹ pẹlu ẹyin
yoruba
female
18-29
phase 2
MZLHM
Àwọn ènìyàn máa ń fi àtẹ̀jíṣẹ́ ránṣẹ́ lórí WhatsApp.
yoruba
male
18-29
phase 2
COA80
Tólá ma yarun rè kótó gérun rè
yoruba
male
30-over
phase 1
IF56O
Tosin ni ló párásitámòl nitóri óni órififò
yoruba
female
18-29
phase 2
OZ82A
Rufus ta ìrù ní ọjà
yoruba
male
30-over
phase 1
7OOK5
Ó máa fọ àwo ìyàgbẹ́ pẹ̀lú ọṣẹ àti omi ní ọla.
yoruba
female
30-over
phase 1
3ZLV0
Zam a si máa din adìyẹ àti ìrẹsì náà.
yoruba
male
30-over
phase 1
VX0F4
Wọn tí gbé afọ́jú náà lọ sí ilé ìtọ́jú àwọn afọ́jú
yoruba
female
18-29
phase 1
070W7
Oṣù mẹ́fà ni Àdìgún fi kọ́ṣẹ́ gbàjámọ̀
yoruba
female
30-over
phase 1
FTOYC
Bẹẹni, mo jó ní àárin ìlú.
yoruba
female
18-29
phase 1
ZHR4X
Mo ṣubú nínú balùwẹ́
yoruba
female
18-29
phase 2
MXTT9
Wọ́n sì sọ fun nípa ìjákulẹ̀ àti ìmófo ìjọba olómìnira.
yoruba
male
30-over
phase 2
GQF2Y
Tí mo bá ní ọmọbìnrin, Màá sọ ọ́ ni Mofifoluwa.
yoruba
female
18-29
phase 1
Z4FYP
Wọ́n máa ń ṣe àtẹ̀jáde ìwé ìròyìn sórí pépà
yoruba
female
18-29
phase 1
8BYBS
Iṣẹ́ ọnà máa ń wáyé ní orísiríṣi àwọ̀.
yoruba
male
18-29
phase 1
HUR4D
Àti ìbílẹ̀ àti òke òkun ni wọ́n n ṣe eré ìjàkadì
yoruba
female
30-over
phase 1
6P5HO
Tola sọ wípé omi náà ti tàn
yoruba
female
6-17
phase 1
W5H7H
Dèfídò ni olórin tí mo fẹ́ràn jù.
yoruba
male
30-over
phase 1
YT0T2
Ọ̀gẹ̀dẹ̀ máa fi ọmọ rẹ̀ rọ́pò ní ọkọ, okòwò tó dára ni.
yoruba
male
18-29
phase 2
FA5M6
Kínní ẹ̀ n wo lori ẹrọ amohunmaworan?
yoruba
female
18-29
phase 1
43FB0
Tani yóò kó gbogbo ìdọ̀tí wọ́nyìí sínú àpẹrẹ ìdọ̀tí?
yoruba
female
30-over
phase 2
YEI1F
Àwọn ènìyàn mìíràn kò mọ̀ nípa dídábẹ títí di òní.
yoruba
male
18-29
phase 1
Z4L9W
Ṣé Bọlá ni ó fẹ́ pa àálọ́ lọ́la?
yoruba
male
30-over
phase 1
UN6VG
Loratidín jẹ́ Ògùn tí wọ́n fín tọ́jú kàtá
yoruba
female
30-over
phase 1
End of preview. Expand in Data Studio
README.md exists but content is empty.
Downloads last month
-