query stringlengths 25 56 | positive sequencelengths 1 4 | negative sequencelengths 6 9 | cluster int64 0 4 |
|---|---|---|---|
Odun wo ni wọn ṣe idije Olympiiki akọkọ? | [
"Àwọn Ìdíje Òlímpíkì\nAwon idije olympiki (ede Greeki: Ολυμπιακοί Αγώνες; Olympiakoi Agones) akoko waye ni odun 776 BC ni ilu Olympia ni ile Greesi."
] | [
"Àwọn Ìdíje Òlímpíkì\nIdije Olympiki {tabi Olympiki} je opolopo ere idaraya ti won sele ni igba ooru ati igba otutu. Won n sele lekan larin odun merin. Titi di 1992, ninu odun kanna ni won n sele. Lat'igbana won ti ya won soto pelu odun meji.",
"Àwọn Ìdíje Òlímpíkì Ìgbà Oru 2004\nLeyin isele adaniloro Osu kesan 2... | 1 |
Orile ede wo ni Washington DC wà? | [
"Washington Wizards\nWashington Wizards ni egbe agbaboolu alapere to budo si ilu Washington D.C. ni Orile-ede Amerika."
] | [
"Betty Williams\nWilliams ṣe olori Ile -iṣẹ Awọn ọmọde Agbaye ati pe o jẹ Alakoso Ile -iṣẹ Aanu Agbaye fun Awọn ọmọde International. O tun jẹ Alaga ti Ile -ẹkọ fun Tiwantiwa Asia ni Washington DC [3] O ṣe ikẹkọ ni ibigbogbo lori awọn akọle ti alaafia, eto-ẹkọ, aṣa-laarin ati oye igbagbọ-igbagbọ, alatako, ati awọn ẹ... | 3 |
Ipa wo ni Benito Mussolini se ni Ogun World War 2? | [
"Benito Mussolini\nÀwọn ọmọ ogun Mussoline kọlu Ethopia ní 1905 wọ́n sì ṣẹ́gun ibẹ̀ lẹ́yìn ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìjà tí ó gbóná. Kò pé tí Mussolini ní kí àwọn ọmọ ogun òun lọ ran General Franco lọ́wọ́ nínú ogun abẹ́lé ilẹ̀ Spain. Ní 1940, Italy bẹ̀rẹ̀ síí kópa nínú ogun àgbáyé kejì. Italy dúró gbá gbá gba ti Germany ṣùgbọ́n w... | [
"Benito Mussolini\nBenito Mussolini je oloselu omo orile-ede Italia. Wọ́n bí Benito ní 1883. Ó kú ní 1945. Òun ni ó dá Fasisti sílẹ̀ ní Italy. Òun ni ó darí Italy ní 1922 sí 1943. Agbára ni ó fi ń darí ilẹ̀ náà (a dictator). It Duce tí ó dúró fún olórí (the leader) ni àwọn èyìn rẹ̀ máa ń pè é. Mussolini àti ìgbìmọ̀... | 4 |
ẹgbẹ wo ni Huey Newton da silẹ? | [
"Huey P. Newton\nHuey Percy Newton (February 17, 1942 – August 22, 1989) je omo ile Amerika. Newton je oludasile ati olori egbe oselu Black Panther Party."
] | [
"Black Panther Party\nHuey P. Newton ati Bobby Seale ni won da sile ni osu kewa odun 1966 ni Oakland ni Kalifọ́rníà.",
"Isaac Newton\nIsaac Newton (tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹrin oṣù kìíní ọdún 1643 - ọjọ́ kọkànlélọ̀gbọ̀n oṣù kẹta 1727) jẹ́ onímọ̀ sáyẹ́nsì ọmọ orílẹ̀-èdè Gẹ̀gẹ̀ẹ́sì. Ó jẹ́ amọ̀ye ninu ẹ̀kọ́ ìsirò, awòrà... | 2 |
Ilu wo lo tobi ju lọ ni orile-ede Poland | [
"Kraków\nKraków ( ), bakanna Krakow or Cracow ( ), je ilu titobijulo keji ni orile-ede Poland"
] | [
"Pólándì\nAjoni yi wo ni 1795, be sini Poland je pipin larin Ile-Oba Prussia, Ile-Oluoba Rosia, ati Austria. Poland pada gba ilominira ni Igba Oselu Keji Poland ni 1918, leyin Ogun Agbaye Akoko, sugbon o je didurolori latowo Jẹ́mánì Nazi ati Isokan Sofieti nigba Ogun Agbaye Keji. Poland pofo emin awon eniyan toju e... | 4 |
Ki ni oluiilu orile ede Japan? | [
"Japan\nJapan jẹ́ arkipelago àwọn Erékùṣù 6,852. àwọn erékùṣù ibẹ̀ tí ó tóbi jùlọ ní Honshū, Hokkaidō, Kyūshū àti Shikoku, ti àpapọ̀ wọ́n jẹ́ èdè mẹ́tàdínlọ́gọ́rùún (97%) ìtóbi ilẹ̀ Japan. Opo awon erekusu wonyi je oloke, opo je onileru; fun apere, ibi gigajulo ni Japan, Oke Fuji, je onileru. Japan je orile-ede ike... | [
"Omobola Johnson\nỌmọbọla Olubusọla Johnson (bii ni ọjọ kẹjidinlọgbọn oṣu kefa ọdun 1967) je omo orile ede Naijiria. O je ikan ninu awon oni imo tekinology, oun pelu si ni alaga egbe Alliance for Affordable Internet (A4AI). O je ojise isọrọ tekinology tele ni abe akoso olori orile ede Goodluck Jonathan. .",
"John... | 4 |
ọdún wo ẹlẹsẹ ti a mọ sí Dick Tiger ṣ'aláìsí? | [
"Dick Tiger\nDick Tiger (orúkọ àbísọ Richard Ihetu; August 14, 1929 – December 14, 1971) jẹ́ ajẹ̀sẹ́ tó gba World Middleweight àti World Light Heavyweight Championships."
] | [
"Dick Tiger\nWọ́n fi orúkọ Tiger sínú Ilé Olókìkí Ìjẹ̀sẹ́ Àgbáyé ní 1991. Ìwé-ìròyìn \"The Ring\" pèé ní Fighter of the Year (Ajẹ̀sẹ́ Ọdún) ní 1962 àti 1965, bẹ́ẹ̀sìni Boxing Writers Association of America (Ẹgbẹ́ Oníròyìn Ìjẹ̀sẹ́ Amẹ́ríkà) pèé ní Fighter of the Year (Ajẹ̀sẹ́ Ọdún) ní 1962 àti 1966. Ní 2002, Ìwé-ìrò... | 1 |
ilu wo lo tobi julọ ni orile-ede Mauritania? | [
"Nouakchott\nNouakchott (Arabic: \"or\" ni oluilu ati ilu totobijulo ni orile-ede Mauritania."
] | [
"Historic Centre of Lima\nNinu ilẹ yi, eleyii to je okan lara awọn ilu to pẹ julọ ni ilu na, ibẹ ni Oidor gbe, eni tí ọba ti spain fún ni aṣẹ lati ma pasẹ ni igba ijoba amunisin. Oidor nipasẹ iṣẹ ni lati rekoja lo sí àgbègbè ibi tio ti lo agbára ìjọba rẹ. Ni ọrọ kan na, ọ ma gba viceroy ni iyànjú gẹgẹbi afọrọlọ.",
... | 4 |
kí ni olú ìlú orile ede Puerto Rico? | [
"San Juan, Púẹ́rtò Ríkò\nSan Juan (, , láti \"San Juan Bautista\" \"Jòhánnù Onítèbomi Mímó\") ní olúìlútitóbijùlo ní Puerto Rico. Juan Ponce da sílè ní odún 1521. Orúkọ áílándì ní Púẹ́rtò Ríkò, tí orúkọ ìlú s̀i jẹ San Juań. San Juan ní ibi gbóógì méta: San Juan àtijó, bííṣì àti agbègbè ríṣọ́ọ́tì àti bẹẹbè lọ. Óhun ... | [
"Egbé Osèlú Olómìnira tí Puèrtó Ríko\nEgbé Osèlú Olómìnira tí Puèrtó Ríko jẹ́ ègbé òsèlú ni orílè-èdè Puerto Rico.",
"Púẹ́rtò Ríkò\nPúẹ́rtò Ríkò (ede Spein for \"Rich Port\"), fun ise ijoba bi Kajola ile Puerto Riko (Commonwealth of Puerto Rico) (, \"Free Associated State of Puerto Rico\") ati nigbakan bi Porto R... | 3 |
Awon orile ede wo ni won pe ni Balkani? | [
"Sérbíà\nSérbíà ( ), fun ibise gege bi orile-ede Olominira ile Serbia (), je orile-ede alafileyika to budo si oritameta Arin- ati Apaguusuilaorun Europe, to gbale apaguusu Pannonian Plain ati apa arin Balkani. Serbia ni bode pelu orile-ede 8, Hungary ni ariwa; Romania, Bulgaria ni ilaorun; orile-ede Makedonia ni gu... | [
"Benin\nIkan ninu awon orile-ede tokerejulo ni Iwoorun Afrika ni Benin. O kere ni ilopo mejo si Naijiria to ni bode mo si ilaoorun. Sugbon o tobi ni ilopo meji si Togo to ni bode mo si iwoorun. Maapu ile Benin fihan pe awon oke re ko fi be yato si ara won (idasarin awon oke re je ).",
"Bósníà àti Hẹrjẹgòfínà\nBós... | 3 |
Odun wo ni Andy Ruiz ati Anthony Joshua ja? | [
"Anthony Joshua\nAnthony Olúwafẹ́mi Ọláṣeéní Jóṣúà (tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹẹ̀ẹ́dógún oṣù kẹwàá odun1989) jẹ́ gbajúmọ̀ Ajẹ̀ṣẹ́ ọmọ bíbí ṣagámù ni ìpínlẹ̀ Ògùn orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, ṣùgbọ́n tí ó ń ṣojú orílẹ̀ èdè Gẹ̀ẹ́sì gẹ́gẹ́ bí ajẹ̀ṣẹ́. Òun ni Ajẹ̀ṣẹ́, Ẹlẹ́ṣẹ̀ẹ́ (Afẹ̀ṣẹ́ kù bí-òjò) tó lágbára jùlọ ni àgbáyé lọ́wọ́́lọ... | [
"Olabiyi Yai\nOlabiyi Babalola Joseph Yaï (ojoibi 1942) je omo ile Benin ati ojogbon litireso ni eka-eko Ede ati Litireso Afrika, OAU, Ife, Nigeria. Odun 1988 ni oluko yii fi eyin ti ni eka-eko yii. Lowolowo Yai ni asoju orile-ede Benin si UNESCO, be si ni o tun je alaga igbimo apase re.",
"T. B. Joshua\nTèmítọ́p... | 1 |
ọmo orile ede wo ni John Locke? | [
"John Locke\nJohn Locke (; 29 Osu Kejo 1632 – 28 Osu Kewa 1704), to gbajumo gege bi \"Baba Isealainide\", je amoye ati onisegun ara Ilegeesi to je ikan larin awon onironu Olaju to ni ipa julo. Won gba bi ikan lara awon aseoniriri akoko ara Britani, nipa titele asa ti Francis Bacon bere, bakanna o tun se pataki si e... | [
"John Lewis\nJohn Robert Lewis (February 21, 1940 – July 17, 2020) je oloselu omo orile ede America, ati ajija gbara ti o je asoju ni ile igbimo asofin Goeorgia lati odun 1987 si odun 2020 ti o fi di oloogbe.",
"Omobola Johnson\nỌmọbọla Olubusọla Johnson (bii ni ọjọ kẹjidinlọgbọn oṣu kefa ọdun 1967) je omo orile ... | 3 |
ọjọ meloo lo wa ninu oṣu february? | [
"Oṣù Kejì\nOsù Keji ni February je ninu Kalenda Gregory. Ojo mejidinlogbon tabi mokandinlogbon ni o wa ninu February."
] | [
"Wọlé Òjó\nWọlé Òjó ni wọ́n bí ní ọjọ́ Kẹfà oṣù Kẹfà, ọdún 19884.(bí 6 Okudu 1984). Ójẹ́ òṣèré jẹ oṣere orí ìtàgé ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà. Ó dìlú mọ̀ọ́ká ní inú iṣẹ́ sinimá nílẹ̀ Nàìjíríà ní ọdún 2009, lẹ́yìn tí ó gbé ipò kẹ́rin nínú ìdíje Amstel Malta Box Office.",
"Tiwa Savage\nNi oṣu kẹfa, ọdun 2014, Savage ṣiṣẹ pap... | 4 |
Ọdún wo ni Namadi Sambo jẹ Gomina ipinle Kaduna ? | [
"Mohammed Namadi Sambo\nMohammed Namadi Sambo (ojoibi August 2, 1954) je oloselu omo orile-ede Naijiria ati Igbákejì Ààrẹ ilẹ̀ Nàìjíríà tele fun ijoba Aare Goodluck Jonathan. O tun ti je Gomina Ipinle Kaduna lati 2007 titi de 2010."
] | [
"Àkójọ àwọn Gómìnà Ìpínlẹ̀ Kàdúná\nAtojo awon alamojuto ati awon Gomina Ipinle Kaduna. Ipinle Kaduna je didasile ni 27 May 1967 bi North Central State o si je titunsoloruko ni 17 Mar 1976 bi Ipinle Kaduna.",
"Ọlágúnsóyè Oyinlọlá\nỌlágúnsóyè Oyinlọlá (ojoibi February 3, 1951) je omo ologun to tifeyinti ati oloselu... | 1 |
Awon orile ede wo lo yika Austria? | [
"Austríà\nAustríà ( tabi ; ), lonibise bi Orileominira ile Austria (German: \"Republik Österreich\"), je orile-ede atimo ile to ni awon eniyan bi egbegberun 8.8 to wa ni Aringbongan Europe. O ni bode mo Orileominira Tseki ati Jemani ni ariawa, Slofakia ati Hungari ni ilaorun, Slofenia ati Italia ni gusu, ati Switsa... | [
"Austríà\nLoni, Austríà je oseluarailu asoju parliamentary|onileasofin to ni awon ipinle mesan. Oluilu ati ilu re totobijulo, pelu iyeolubugbe to ju egbegberun 1.6, ni Vienna. Austríà je ikan ninu awon orile-ede to lolajulo lagbaye, pelu IO oloruko ti enikookan to je $43,723 (idiye 2010). Orile-ede ohun ti sedagbas... | 3 |
oṣù wo ni keresimesi má ń bọ́ sí? | [
"Christmas\nChristmas tí Yorùbá ń pè ní ọdún Kérésìmesì jẹ́ ọdún ọjọ́ ìbí Jésù. Wọ́n máa ń ṣe ọdún yìí ní ọjọ́ karùndínlọgbọ̀n oṣù kejìlá tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn maa ń ṣe kákàkiri àgbáyé."
] | [
"Àjàkálẹ̀-àrùn COVID-19 ní Málì\nNí ọjọ́ kejídínlógún oṣù kẹta, Ààrẹ Ibrahim Boubacar Keita dá àwọn ọkọ̀ òfurufú tí wọ̀n ń bọ̀ láti orílẹ̀-èdè tí àjàkálẹ̀ àrùn yí ti ń ṣẹlẹ̀ dúró. Ààrẹ tún ti àwọn ilé-ẹ̀kọ́ pa, ó sì fagilé àwọn àpèjọ tí ó bá tóbi. Síbẹ̀síbẹ̀, àwọn ìdìbò tí wọ́n ti gbèrò pé yí ò wáyé ní oṣù kẹta sí ... | 4 |
Egbe oloselu wo ni Boris Johnson wa pẹlu? | [
"Boris Johnson\nAlexander Boris de Pfeffel Johnson (; born 19 June 1964) jẹ́ olóṣèlú ará ilẹ̀ Britènì tí ó wà nípò àṣẹ Alákòóso Àgbà ilẹ̀ Britènì àti Aṣíwájú ẹgbẹ́ òṣèlú the Conservative Party lọ́wọ́lọ́wọ́, lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú Egbe Oselu Conservative láti July 2019."
] | [
"Rodney Joseph Johnson\nLeyinn ti Quintero yinbo gbemi Johnson, kia ni won ti mu ti wo si fi si ahamo awo olopaa . O bebe pe oun ko moomo paa lati wipe ori ou ko pe rara. Adajo ti o gbo ejo naa ko teti gbo oro enu re, o si dajo ewon gbere fun ni odun 2008. Ewe, o btun je okan lara awon ti owo te lasiko ti won ... | 4 |
ọdún wo ni Emomali Rahmon di ààrẹ Orile ede Tajikistan? | [
"Emomalii Rahmon\nEmomalii Rahmon (Tajik: ; ; Russian: Эмомали Рахмон) (ojoibi October 5, 1952) ti wa ni ipo olori orile-ede ile Tajikistan lati 1992, ati gege bi Aare lati 1994."
] | [
"Rahmon Adédoyin\nỌmọba Rahmon Adégòkè Adédoyin ẹni tí wọ́n bí ní ọjọ́ Kínì oṣù Kíní, ọdún 1957 (born January 1, 1957) jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè is a Nàjíríà. Olùkọ́ni, àti bajú-gbajà oníṣòwò ,bákan náà ni ó jẹ́ olùdásílẹ̀ iké-ẹ̀kọ́ Fásitì Odùduwà àti ilé-ẹ̀kọ́ gbogb-nìṣe Polytechnic, ní Ilé-Ifẹ̀ Nínú ìtàkurọ̀sọ rẹ̀ pẹ̀lú... | 3 |
ipinlẹ wo ni Isiala Ngwa wa ni Nàìjíríà? | [
"Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Àríwá Isiala-Ngwa\nAgbegbe Ijoba Ibile Ariwa Isiala-Ngwa je ijoba ibile ni Ipinle Abia to wa ni Naijiria.",
"Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Gúúsù Isiala-Ngwa\nAgbegbe Ijoba Ibile Guusu Isiala-Ngwa je ijoba ibile ni Ipinle Abia to wa ni Naijiria."
] | [
"Àjàkálẹ̀ àrùn COVID-19 ní ilẹ̀ Nàìjíríà\nNí ọjọ́ kẹsan an oṣù kẹrin, Ìjọba Ipinlẹ Kwara fi òfin de lílọ àti bíbọ̀ àwọn ènìyàn ni Ipinlẹ wọn fún ọjọ́ mẹ́rìnlá bẹ̀rẹ̀ láti ọjọ́ kẹwàá oṣù kẹrin. Ìjọba fi ààyè gbà àwọn ti wọn n ta ounjẹ àti oogun láti ṣe iṣẹ́ ni ọjọ́ Ajé, ọjọ́ Rú, àti ọjọ́ Ẹtì laarin aago mẹ́wàá òwúrọ... | 4 |
Ipinle wo ni ilu Orlu wa? | [
"Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Orlu\nAgbegbe Ijoba Ibile Orlu je ijoba ibile ni Ipinle Imo ni Naijiria. Ibujoko re wa ni Orlu"
] | [
"Àwọn àdúgbò ìlú Mọdákẹ́kẹ́\nOruko ati itumo awon adugbo ilu Mọdákẹ́kẹ́, ni Ipinle Osun, Naijiria.",
"Ìlú Ọ̀wọ̀\nOwo je ikan lara awon ijoba ibile ni ipinle Ondo. Oba Owo ni won n pe ni olowo ti Ilu Owo. Oba ti o wa lori ite lowolowo ni Ajibade Gbadegesin Ogunoye.",
"Uche Elendu\nElendu, botilẹjẹpe o ti kọ iyaw... | 4 |
Odun wo ni won da egbe World Health Organization silẹ? | [
"Àjọ Ìlera Àgbáyé\nWọ́n dáa WHO sílẹ̀ ní Ọjọ́ keje Oṣù kẹrin Ọdún 1948. Ipade akoko ti apejo ilera agbaye, ajo ti o n sakoso WHO, waye ni ojo kerinlelogun osu keje odun naa. Àjọ Ìlera Àgbáyé gba awon dukia, osise, ati ojuse Ajo Ilera ti Ajumose Orilede, ile-ise agbaye d'Hygiène Publique, ati isori ailera gbogboogbo... | [
"Àjàkálẹ̀ àrùn Covid-19 lórílẹ̀-èdè Olómìnira Benin\nLọ́jọ́ Kejìlá oṣù kìíní ọdún 2020 ni àjọ elétò ìlera àgbáyé, World Health Organization (WHO) jẹ́rìí pé ẹ̀rànkòrónà, Covid-19, ni ó ń fa àìsàn èémí láàárín àwọn ènìyàn kan lágbègbè Wuhan,ní Ìpínlẹ̀ Hubei, lórílẹ̀-èdè China, èyí tí wọ́n jábọ̀ rẹ̀ fún àjọ WHO lọ́jọ́... | 1 |
Orile ede wo ni San Marino wa? | [
"San Màrínò\nSan Màrínò je orile-ede ni orile Europe."
] | [
"El Marino (1917)\nEl Marino jẹ́ ìwé ìròyìn ojoojúmọ́ ní orílẹ̀-èdè Tsílè tó jẹ́ dídásílẹ̀ ní ọdún 1917 tó jẹ́ títẹ̀jáde ní ìlú Pichilemu.",
"Siẹrra Léònè\nSiẹrra Léònè () (Krio: \"Sa Lone\"), lonibise bi Orile-ede Olominira ile Siẹrra Léònè, je orile-ede ni Iwoorun Afrika. O ni bode mo Guinea si ariwa ati ilaoru... | 3 |
Ta ni Aarẹ orile ede Ivory Coast? | [
"Nàìjíríà\nNí ìtẹ̀síwájú pẹ̀lú u òfin òkèèrè tó so mọ́ Áfríkà, Nàìjíríà mú àbá wá fún níná owó kan náà ní Ìwọ̀oòrùn Áfríkà tí á máa jẹ́ \"Eco\" lábẹ́ ẹ èrò pé náírà ló máa wò ó dàgbà ṣùgbọ́n ní ọjọ́ kọkànlélógún, oṣù Ọ̀pẹ, 2019; Ààrẹ Alassane Ouattara ti Ivory Coast pẹ̀lú u Emmanuel Macron àti púpọ̀ nínú àwọn orílẹ... | [
"Côte d'Ivoire\nCôte d'Ivoire tabi Orile-ede Olominira Côte d'Ivoire (tele bi Ivory Coast) je orile-ede ni apa iwo oorun Afrika to ni bode mo Liberia ati Guinea si iwo oorun, Mali ati Burkina Faso si ariwa, Ghana si ila oorun ati Ikun-odo Guinea ati Okun Atlantiki si guusu.",
"Fatoumata Diawara\nIlu Ivory Coast n... | 3 |
Odun wo ni Augusto Pinochet je aare orile-ede Chile? | [
"Augusto Pinochet\nAugusto José Ramón Pinochet Ugarte, to gbajumo lasan bi Augusto Pinochet (), (25 November 1915 – 10 December 2006) je Ogagun ajagun ara Chile ati apase to fipa gbajoba ninu kuupu 11 September 1973. He was the Commander-in-Chief of the Chilean army from 1973 to 1990, president of the Government Ju... | [
"Afonso Augusto Moreira Pena\nAfonso Augusto Moreira Pena je omo orile-ede Brasil ati Aare orile-ede Brasil tele.",
"Augusto Hamann Rademaker Grünewald\nAugusto Hamann Rademaker Grünewald (Rio de Janeiro, May 11, 1905 - September 13 1985) je omo orile-ede Brasil ati Aare orile-ede Brasil tele.",
"Augusto Tasso ... | 1 |
Odun wo ni Jolly nyame je gomina ipinle taraba? | [
"Jolly Nyame\nJolly Nyame (à pè já -Jolly Tavoro Nyame) jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Naijiria, láti ìjọba ìbílẹ̀ Zing, ní Ìpínlẹ̀ Tàràbà. A bi ni ọjọ́ kẹẹdọgbọn, oṣù Kejìlá ọdún 1955. Ó ti fi ìgbà kan jẹ́ gomina Ipinle Taraba (ọjọ́ kọkàn-dín-lọ́gbọ̀n, oṣù karùn, ọdún 1999 títí di ọjọ́ kọkàn-dín-lọ́gbọ̀n, oṣù karùn, ọdún 2007... | [
"Udom Gabriel Emmanuel\nUdom Gabriel Emmanuel (ojoibi 11 July 1966) ni gomina Ipinle Akwa Ibom ni Naijiria, o wa lori aga lati 29 May 2015 leyin igbatowe leyin idibo April 2015 labe egbe oloselu People's Democratic Party. Won tun tundiboyan sipo gomina ni ojo 29k osu karun odun 2019.",
"Ọlágúnsóyè Oyinlọlá\nỌlágú... | 1 |
kí ni oluilu orile-ede griisi? | [
"Gíríìsì\nGriisi je orile-ede adagbasoke to ni Human Development Index giga, Griisi ti je omo egbe Isokan Europe lati 1981 ati Isokan Okowo ati Owonina Europe lati 2001, NATO lati 1952, ati Ile-ise Ofurufu Europe lati 2005. Bakanna o tun je omo egbe latibere Isodokan awon Orile-ede, OECD, ati Agbajo Ifowosowopo Oko... | [
"Tbilisi\nTibilisi ni oluilu orile-ede Georgia.",
"Conakry\nKonakri je oluilu orile-ede Guinea.",
"Gùyánà\nGùyánà ( ), lonibise bi Orílẹ̀-èdè Olómìnira Aláfọwọ́sowọ́pọ̀ ilẹ̀ Gùyánà, je orile-ede alase ni etiomi apaariwa ni Guusu Amerika. Asa re je ko jo awon Eledegeesi Karibeani be sini o je ikan ninu awon oril... | 4 |
Omo orile-ede wo ni osere Yvonne Nelson? | [
"Yvonne Nelson\nYvonne Nelson (ti a bi ni ojo kejila osu kankanla ni odun 1985) jẹ oṣere ara ilu Ghana, awoṣe, o nse fiimu ati iṣowo . O ti ṣe irawọ ni ọpọlọpọ awọn fiimu, gegebi \"\" ( (2013),\"Any Other Monday\", \"In April\", and \"Swings\"."
] | [
"Yvonne Orji\nYvonne Anuli Orji (bíi ni ọjọ́ kejì oṣù kejìlá ọdún 1983) jẹ́ òṣèré ni orílẹ̀ èdè Nàìjíríà àti Amẹ́ríkà. Ó gbajúmọ̀ fún ipá tí ó kó nínú eré Insecure ní ọdún 2016, èyí tí ó jé kí wọn yàán fún àmì ẹ̀yẹ tí Primetime Emmy Award àti NAACP Image Awards.",
"Yvonne Nelson\nYvonne Nelson ni a fun ni ami eye... | 2 |
Ọdún wo ni Pope John Paul s'alaisi? | [
"Pópù Jòhánù Páúlù Èkejì\nThe Venerable Pope John Paul II (, , , , ), born Karol Józef Wojtyła (; 18 May 1920 – 2 April 2005) served as Supreme Pontiff of the Catholic Church and Sovereign of Ìlú Fatikan from 16 October 1978 until his death over 26 years later."
] | [
"Paul Keating\nPaul John Keating (ojoibi 18 January 1944) je Alakoso Agba orile-ede Austrálíà tele.",
"Paul Adefarasin\nPaul Adefarasin ni a bi ojo karùnlelọgún Oṣu Kini Ọdun 1963 jẹ iranṣẹ Kristiẹni ati olukọ tẹlifisiọnu. Oun ni oludari House On The Rock Church. House on the Rock church je olugbalejo \"The Exper... | 1 |
ọdun wo ni Julius Caesar ku? | [
"Caligula\nGaius Julius Caesar Augustus Germanicus (31 August AD 12 – 24 January AD 41), jé gbajúmò pèlú agnomen Caligula (), jé Oba alayé ilè Róòmù, ó joba láti ojo Kerìndínlógún osù Kéta 1837 16 March 37 títí tí wón fi [[assassination|sekúpa] ní 24 January 1841.",
"Juliu Késárì\nGaiu Juliu Késárì (13 July 100 ... | [
"Augustus\nGaius Julius Caesar Augustus (23 September 63 BC – 19 August AD 14) ni olori akoko Ile Obaluaye Romu, to jaba le lori lati January 27 kJ titi di ojo iku re ni 14 lJ. Bibi gege bi Gaius Octavius Thurinus, o je gbigba bi omo posthumously latowo egbon-baba-baba re Gaius Julius Caesar leyin igba to ku ni 44 ... | 0 |
Odun wo ni King Leopold ṣ'alaisi? | [
"Leopold 2k ilẹ̀ Bẹ́ljíọ̀m\nLeopold 2k (, ) (9 April 1835 – 17 December 1909) lo je Oba awon ara Beljiom keji. Won bi ni Brussels gege bi omokunrin keji Leopold 1k ati Louise-Marie of Orléans, o joba leyin baba re ni 17 December 1865 titi di ojo iku re."
] | [
"Otto von Bismarck\nOtto Eduard Leopold von Bismarck (1 April 1815 – 30 July 1898) je asiwaju ara Prussia/Jemani ti opin orundun 19th, ati eni pataki ni aye igbana. Gege bi \"Ministerpräsident\", tabi Alakoso Agba ile Prussia lati 1862–1890, o samojuto iparapo ile Jemani. O seilale Ile Obaluaye Jemani ni 1871, o si... | 1 |
Ki ni oruko ṣọọsi Paul Adefarasin? | [
"Paul Adefarasin\nPaul Adefarasin ni a bi ojo karùnlelọgún Oṣu Kini Ọdun 1963 jẹ iranṣẹ Kristiẹni ati olukọ tẹlifisiọnu. Oun ni oludari House On The Rock Church. House on the Rock church je olugbalejo \"The Experience\" Orin ihinrere Paul Adefarasin ni abi ni 25 osu Kini Ọdun 1963 si Joseph Adefarasin. Adajọ ile-ẹj... | [
"Paul Adefarasin\nAdefarasin ti kọwe, iwe ti otiko ju 20 lo awọn iwe kekere Christian iwuri ati orisun iwuri fún ọpọlọpọ.distributors.",
"Paul Adefarasin\nAdefarasin lọ si Ile-iwe St Saviour ni Ikoyi ati Ile-ẹkọ Igbobi niYaba, ni Èkó. Oka iwe ni unifasiti miami ibi tí ó gba Apon tí fàáji. O ṣe adaṣe ni Florida ṣa... | 1 |
Ki ni olu-ilu orile-ede Egypt? | [
"Káírò\nKairo je oluilu ile Egypti."
] | [
"Ùgándà\nÙgándà tabi orile-ede Olominira ile Uganda je orile-ede ni apa ilaoorun Afrika. O ni bode pelu orile-ede Kenya.",
"Orílẹ̀-èdè Olómìnira Olóṣèlú Ará ilẹ̀ Ethiópíà\nOrílẹ̀-èdè Olómìnira Olóṣèlú Ará ilẹ̀ Ethiópíà ni oruko onibise ile Ethiopia lati 1987 de 1991, gegebi bi o se je didasile latowo ijoba Kommun... | 4 |
ọdun wo ni Pope John Paul ṣ'alaisi? | [
"Pópù Jòhánù Páúlù Èkejì\nThe Venerable Pope John Paul II (, , , , ), born Karol Józef Wojtyła (; 18 May 1920 – 2 April 2005) served as Supreme Pontiff of the Catholic Church and Sovereign of Ìlú Fatikan from 16 October 1978 until his death over 26 years later."
] | [
"Pópù Jòhánù Páúlù Èkínní\nPope John Paul I je Popu Ìjọ Kátólìkì tele.",
"Paul Keating\nPaul John Keating (ojoibi 18 January 1944) je Alakoso Agba orile-ede Austrálíà tele.",
"Paul Udogu\nPaul Udogu jẹ́ bíṣọ́ọ́ọ̀bù ìjọ Anglican ni orílẹ̀-èdè Nàìjíríà: Ó sì jẹ́ bíṣọ́ọ́ọ̀bù ti ẹ̀ka Afikpo, láti ọdún 2010.",
"Pa... | 1 |
Oṣù wo ni ọdún 1967 ni ogun Biafra bẹrẹ? | [
"Ogun Abẹ́lé Nàìjíríà\nOgún Abẹ́lé Nàìjíríà wáyé láàárín ọjọ́ Kẹfà Oṣù Okúdù Ọdún 1967 sí ọjọ́ kẹẹ̀dógún oṣù Ṣẹ́ẹ́rẹ́: tí a tún mọ̀ sí (Ogun Nàìjíríà - Biafra tàbí Ogun Biafra) jẹ́ Ogun Abẹ́lé tí ó wáyé láàárín ìjọba Nàìjíríà àti orílè-èdè Biafra, Ìpínlẹ̀ tí ó fé dádúró tì ó ti fẹ́ gba òmìnira kúrò lára Nàìjíríà ní... | [
"Odumegwu Ojukwu\nChukwuemeka Odumegwu-Ojukwu (a bíi ní ọjọ́ kẹrin oṣù kọkànlá ọdún 1933 - ó sì kú ní ọjọ́ kẹrìndínlọ́gbọ̀n oṣù kọkànlá ọdún 2001)jẹ́ jaguanjg àti òsèlú ọmọ orílẹ̀-Nàìjírà tẹ́lẹ̀ . Ó fìgbà kan jẹ Gómìnà ológun apá àríwá Nàìjíríà lọ́dún 1966. Oun ló ṣe égbátẹrù ogun abẹ́lé Biafra fi tako ìjọba orile-... | 0 |
Odun wo ni wọn da ẹgbẹ United Nations silẹ? | [
"Àjọ àwọn Orílẹ̀-èdè\nÀjọ Ìṣọ̀kan àwọn Orílẹ̀-èdè tabi Àjọ àwọn Orílẹ̀-èdè ni soki (ní èdè Geesi: UNO tàbí UN) jẹ́ àgbájọ káríayé ti eto re je lati fa ifowosowopo ninu ofin kakiriaye, abo kakiriaye, idagbasoke eto inawole, ilosiwaju awujo, eto omoniyan ati imudaju alafia lagaye. OA je didasile ni odun 1945 leyin Og... | [
"Àwọn ẹ̀tọ́ ọmọnìyàn\nero odeoni nipa awon eto omoniyan dide leyin isele Ogun Agbaye Keji, gege bi idahun si Ipaniyanrun àwon Ju, eyi fa itowobowe \"Ìkéde Akáríayé fún àwọn Ẹ̀tọ́ Ọmọnìyàn\" latowo United Nations General Assembly ni 1948.",
"Àdéhùn igi aláwọ̀-ewé\nLọ́jọ́ kẹtàlá oṣù kẹjọ ọdún 2013, àjọ kéréje lábẹ́... | 1 |
Orukọ wo ni a n pe orile-ede Botswana ki wọn to yi pada? | [
"Bòtswánà\nNi orundun 19k, ogun sele larin awon Tswana ti won ti ungbe Botswana ati awon eya Ndebele ti won sese unko bo si agbegbe yi lati ariwa-ilaorun. Bakanna rogbodiyan sele pelu awon ateludo Boer lati Transvaal ni ilaorun. Leyin itoro awon olori Batswana bi Khama III, Bathoen ati Sebele fun iranlowo, Ijoba Br... | [
"Bòtswánà\nBotswana ko ni ju eniyan to to egbeegberun meji lo nitorie o je ikan ninu awon orile-ede alabugbe kekere julo ni agbaye. Nigba ti Botswana gba ilominira latowowo Ilẹ̀ọba Aṣọ̀kan ni 1966, o je ikan ninu awon orile-ede to talaka julo ni Afrika pelu GDP ti enikookan bi US$70. Latigbana Botswana ti yira re p... | 4 |
Ki ni oluilu orile ede Albania? | [
"Albáníà\nAlbáníà je oseluarailu onileasofin pelu itokowo toun yipada. Oluilu Albáníà, Tirana, je ile fun awon eniyan bi 600,000 ninu awon eniyan 3,000,000 to wa lorile-ede na. Atunse oja alominira ti si orile-ede sile fun inawo idagbasoke latokere, agaga fun idagbasoke okun ati eto irinna."
] | [
"Albáníà\nAlbáníà ( , , Gheg Albanian: \"Shqipnia\"/\"Shqypnia\"), lonibise bi Orileominira ile Albáníà (, pipe ; Gheg Albanian: \"Republika e Shqipnísë\"), je orile-ede ni Guusuilaorun Europe, ni agbegbe awon Balkani. O ni bode mo Montenegro ni ariwailaorun, Kosovo ni riwailaorun, Orileominira ile Makedonia ni ila... | 4 |
Kí ni oluilu orile-ede Finland? | [
"Helsinki\nHẹlisíǹkì (sv: Helsingfors) ni oluilu orile-ede Finland."
] | [
"Fínlándì\nFinlandi (pipe ), fun onibise bi Orile-ede Olominira ile Finlandi, je orile-ede Nordik kan to budo si agbegbe Fennoscandia ni Apaariwa Europe. O ni bo de mo Sweden ni iwoorun, Norway ni ariwa ati Russia ni ilaorun, be sini Estonia wa ni guusu re niwaju Ikun-omi Finlandi.",
"Fienna\nVienna (; , Austro-B... | 4 |
Odun wo ni won bi Otto von bismarck? | [
"Otto von Bismarck\nOtto Eduard Leopold von Bismarck (1 April 1815 – 30 July 1898) je asiwaju ara Prussia/Jemani ti opin orundun 19th, ati eni pataki ni aye igbana. Gege bi \"Ministerpräsident\", tabi Alakoso Agba ile Prussia lati 1862–1890, o samojuto iparapo ile Jemani. O seilale Ile Obaluaye Jemani ni 1871, o si... | [
"Kurt Waldheim\nKurt Josef Waldheim ti o je akowe agba fun United Nation Organisation (UNO) laarin odun 1972 - 1982 ti o si tun wa di Aare (president) Austria ni 1986 ku ni 14/6/2007 nigba ti o di omo odun mejidinlaaadorun-un (88).",
"Otto Wallach\nOtto Wallach (27 March 1847 - 26 February 1931) je onimo sayensi ... | 1 |
ọmọ orile ede wo ni Samuel Peters? | [
"Samuel Peter\nSamuel Okon Peter tí wọ́n bí ní Ọjọ́ Karùn-ún oṣù kẹsàn-án ọdún 1980 (September 5, 1980 ní Ìpínlẹ̀ Akwa Ibom, lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà), tí orúkọ ni ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ \"The Nigerian Nightmare,\" jẹ́ eléré ìdárayá ajẹ̀ṣẹ́ ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríàtí ó jẹ́ ajẹ̀ṣẹ̀-àgbà àti olùborí ajẹ̀ṣẹ̀-àgbà àgbáyé WBC níg... | [
"Samuel Ortom\nSamuel Ioraer Ortom tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹtàlélógún oṣù kẹrin ọdún 1961 (23rd April 1961) jẹ́ òṣèlú, oníṣòwò àti aláàánú ọlọ́rẹ ọmọ bíbí ìpínlẹ̀ Benue lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Òun ni Gómìnà Ìpínlẹ̀ Benue lọ́wọ́́lọ́wọ́. Lọ́dún 2015 ló wọlé gẹ́gẹ́ bí gómìnà lábẹ́ àsíyá ẹgbẹ́ òṣèlú APC, nígbà tó di ọdún 201... | 3 |
ọdún wo ni wọn kọkọ bẹrẹ ẹbun Nobel ? | [
"Ẹ̀bùn Nobel\nẸ̀bùn Nobel (\"Ẹ̀bùn Nobel ní èdè Gẹ̀̀ẹ́̀si àti Nobelpriset ní ède Sweden\" Norwegian: \"Nobelprisen\") ní àwọn èbùn odoódún káríayé tí àwọn ìgbìmọ̀ ará Scandinafia ń fún ni fún ìdámọ̀ ìmúlọsíwájú àṣà àti ìmọ̀ ìjìnlẹ̀. Wọ́n jẹ́ dídásílẹ̀ ní ọdún 1895 latowo ara Sweden onímọ̀ ẹ̀kọ́ ẹ̀lá (kẹ́místri) Alf... | [
"Betty Williams\nNi akoko ti o gba ẹbun Nobel, Williams ṣiṣẹ bi olugba ati pe o n gbe awọn ọmọ rẹ mejeeji pẹlu ọkọ akọkọ Ralph Williams. Igbeyawo yi tuka ni ọdun 1981. O gbeyawo oniṣowo James Perkins ni Oṣu kejila ọdun 1982; wọn ngbe ni Florida ni Amẹrika.",
"Amarachi Nwosu\nNí ọdún 2019, Malala Yousafzai tí ó gb... | 1 |
Nibo ni Naijira ni Nok wa? | [
"Àṣà Nok\nÀṣà Nok yo jade ni arin ile Naijiria ni bi odun 1000 SK o si pare lai nidi ni bi odun 200 LK. A ko mo ohun ti awon ènìyàn náà pe ara won, nitori náà oruko àsà náà ni won fi so ilu won. Àsà Nok wa lati ariwa Afrika ni ipinlè Niger.",
"Ìtàn ilẹ̀ Nàìjíríà\nThe Nok culture thrived from approximately 1,500 B... | [
"Nàìjíríà\nÀwọn ará Nok ní ààrin Nàìjíríà se ẹ̀re gbígbẹ alámọ̀ tí àwọn onímọ̀ ayéejọ́un tí wárí. Ère Nok tó wà ní Minneapolis Institute of Arts, júwè é ẹni pàtàkì kan mú \"Ọ̀pá idaran\" dání ní owó ọ̀tún àti igi ní owó òsì. Ìwònyì ní àmì-ìdámọ̀ aláse tó jẹ́ bíbásepọ̀ mò àwọn fáráò ilè Egypti ayéejọ́un àti òrìṣà, O... | 4 |
End of preview. Expand in Data Studio
README.md exists but content is empty.
- Downloads last month
- 6