sentence stringlengths 21 391 |
|---|
Ó yẹ kí fífi ìjilnlẹ̀ Yorùbá kọ àwọn ọmọdé jẹ́ nǹkan ìwúrí fún òbí. |
Ẹgbẹ́ ọmọ Odùduwà ní Alága ti fètò ìdájọ́ sí ọjọ́ Sátidé |
Ọ̀pọ̀ ọ̀dọ́ Nàíjíríà ń bèèrè láti ṣàtìpó ní Ògbómọ̀ṣọ́. |
Ẹwọ́n ọdún méjì ni wọ́n fún àwọn sója mẹ́rin tó pa ènìyàn. |
Ẹgbẹ́ àwọn awakọ̀ ṣe ìpàdé lánàá. |
Olóògbé gbé ìgbé ayé dada nígbàtí ó wà láyé. |
Ìyanulolúwa kò bẹ̀rù àṣẹ ilé ẹjọ́, ó ní kí ẹgbẹ́ má bàjẹ́ ni tòun |
Ìgbòho lọ́wọ́ ní àtìmọ́lé ọlọ́pàá ní Orílẹ́-èdè Nàíjíríà. |
Ìgbà mẹ́ta rèé tí àwọn ọmọ ọ̀dọ̀ ti gé ẹ̀mí ọ̀gá wọn kúrú. |
Àwọn ohun pàtàkì nípa Fẹ́mi ni wón ti sọ. |
Olórí ẹbí àti àwọn ẹbí lè gbéná wojú ara wọn láìpẹ́ lórí ọ̀rọ̀ yìí. |
Adé àti Ọlá padà di ọmọ ilé ìwé wa. |
Apanilẹ́rìí ní àwọn òṣèré tó kú láàrin ọjọ́ méje tó kọjá |
Kí ló mú òjòwú ọ̀rẹ́kùnrin fì ìbínú yìnbọn lu ọ̀rẹ́bìnrin rẹ̀? |
Ìjọba ìpínlẹ̀ Òǹdó ti fẹ́ pàse ẹ̀kọ́ ọ̀fẹ́ fún àwọn akẹ́kọ̀ọ́. |
Kò sí ẹni tó le gba ìtọ́jú nílẹ̀ òkèèrè láì san owó púpọ̀ |
Bùhárí ti sọ ìdí tí àwọn ọmọ orílẹ̀ èdè wa fi ṣe ìfẹ̀hónúhàn |
Gómìnà Mákindé gbàlejò àwọn alùfáà lásìkò ààrùn jẹjẹrẹ. |
Àwọn ajínigbé ya bò wọ́n ní ojú ọ̀nà, wọ́n sì gbé ọmọ kan lọ |
Ìwé tí mo ní kí o kà lọ́jọ́sí, wọ́n ti ṣe é sínu fọ́nrán. |
Ọlọ́pàá kan ti gbọ́ ẹ̀sùn ti wọ́n fi kàn àbúrò ẹ̀ nípa ìbálòpọ̀. |
Olóńgbò bàbah gbé ẹja bàbá jẹ. |
Gbajúgbajà òṣẹ̀ré Òrìṣàbùnmi ti kú. |
Ẹ̀sùn àjẹbánu àti lílo owó báṣubàṣu la fi kàn olóyè náà. |
Àwọn ilé-iṣẹ́ kan lé ọ̀pọ̀ òṣìṣẹ́ kúrò nítorí wọn kò lè san owó. |
Aṣọ agbádá ni bàbá Àbẹ́ní wò wá sí ilé Àjàní. |
Ẹgbẹ́ ọmọ bíbí Òkè Ọya ti ń bẹ̀bẹ̀ àtìlẹyìn fún ṣèyí Máyọ̀wá. |
Aṣáájú ní iléeṣẹ́ ológun ti yabo ibùdó àwọn jàndùkú. |
Ẹgbẹ́ alátakò ni wón. |
Ọwọ́ tẹ afurasí ọ̀daràn kan tí ó fi orúkọ ọba lu jìbìtì |
Ọmọbìnrin kan ti rí ẹran ara èèyàn nínú ilé ọ̀rẹ́kùnrin ẹ̀ |
Àwọn òṣèrè sinimá ti ń gbìnyànjú lórí fífi àmì ohùn sí ọ̀rọ̀. |
Ẹ gbọ́ nǹkan ti agbẹ́jọro sọ lórí ìdájọ tí ó wáyé ní ìlú Òǹdò. |
Ọkùnrin tó lẹ òkuta mọ́ ǹkan ọkùnrin rẹ̀ ti dèrò ọ̀run |
Ìjọba Ọbásanjọ́ ló fi dọ́là san èlé orí gbèsè tí a jẹ |
Iléeṣẹ́ ọmọogun Nàíjíríà ti dárúkọ ọ̀gágun táwọn agbébọn pa. |
Wo bo ṣe le dá ojúlówó àti ẹbu áàpù mọ̀. |
Odòlayé Àrẹ̀mú jẹ́ olórin kan tó gbajumọ̀ ní ìlú Ìlọrin |
Ó dára kí ọmọ ìró afárànma àti agbárànmọ́ fáwẹ́ẹ̀lì Yorùbá. |
Irúfẹ́ òǹkọ̀wé yìí ṣọ̀wọ́n láwùjọ Yorùbá. |
Ẹgbẹ́ wa ké gbànjarè sí ìjọba àpapọ̀ Nàíjíríà. |
Àwọn onílù láàfin ló ń tú ọ̀pọ̀ àṣírí fún òhun láàfin. |
Bàbá Tolú kọ ọ́ pé ọmọ òun ní ìbálòpọ̀ pẹ̀lú obìnrin ẹgbẹ́ rẹ̀. |
Nítorí ìwà ìbàjẹ́ àti àìgbọràn ni mo fi kẹ̀yìn sí gómìnà wa |
Tí o bá gba abẹ́rẹ́ àjẹsára, òtútù kò ní mú ẹ mọ́. |
Ilé ẹjọ́ ti da ẹjọ́ fún Olúwáṣun nítorí pé ó jí ọmọ gbé |
Rẹ̀mi ní owó ti tán lọ́wọ́ òhun. |
Ìdàgbàsókè Ìlú Ẹ̀gbá ló jẹ mí lógún |
Ìyá olóògbé sọ pé kí ìjọba gbé òkú ọmọ òun sílẹ̀ |
Ìpànìyàn wà lára ẹ̀sùn tí wọn fi kan afurasí náà. |
Àlàmú ti mú orin Sólómọ́nì láti kà nínú Bíbélì. |
Mosún gbé ẹjọ́ rẹ̀ lọ sí ilé ẹjọ́ kòtẹ́milọ́rùn lẹ́yìn ọdún kan. |
Ipò alága ìbílẹ̀ ti tọ́ sí Bàbá Ìyábọ̀ àti ẹ̀gbọ́n ẹ̀ |
A tí mú Ọlọ́páà to f'ọ̀nà ẹ̀bùrú gba owó ẹ̀yìn lọ́wọ́ awakọ̀. |
Sanwó-Olu buwọ́lu ìgbésẹ̀ ìjọba láti tún Èkó ṣe. |
Àwọn obìnrin ilé ni wọ́n ń lọ sí ọjà lọ ta gbogbo ẹ̀. |
Omi tútù ni Adé bù fún mi nígbàtí mo bèrè fun omi. |
Alábòsí àti olójúṣàájú ní àwọn akẹẹgbẹ́ mi. |
Olórí Oko ti barajẹ́ nitórí bí ọmọ rẹ̀ ṣé bá àwọn méjì sùn |
Gbogbo èrò tó wá pàdé Mojí nílé ẹ̀ ló bínú síi. |
Òrùka mẹ́fà ní ọkọ́ mi fi béèrè láti fẹ́ mi. |
Ìjọba pàṣẹ ìtìmọ́lé fún òṣìṣẹ́ ìjọba kan tó lú obìnrin kan pa. |
Ìjọba ti ń gbẹ̀rọ ìgbàlódé láti pèsè fún àwọn eléré orí ìtàgé |
Ọkọ bàálù mẹ́ta bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ padà láàrin Nàìjíríà sí Amẹ́ríkà |
Àrùn kòrónà wà lára ìṣẹ̀lẹ̀ ní ọdún méjì sẹ́yìn. |
Tilé tẹkọ̀ létí lọ sí ìlú Ọ̀wọ̀ láti kí Àwọn òbí rẹ̀. |
Mosún jẹ́ ara orúkọ tí a máa ń fún ara wa ní àdúgbò |
Aláàfin Ọ̀yọ́ gba àdúrà ọdún fún àwọn ọmọ Nàìjíríà. |
Igbákeji ààrẹ Yẹmí Òṣíbájò sàbẹwò sí ìyàwó Ajímọ̀bí. |
Oun tí ojú àwọn obìnrin rí nígbà tí wọ́n bá ń bímọ le gidi. |
Àwọn ohun tó ṣókùnkùn sí ọ pọ̀ gidigidi gan. |
Inú ìwé ìròyìn aláròyé ni mo ti rí i ka ni àárọ̀ yìí |
Kí ni ìyàtọ̀ tó wà láàrin ìjálá àti ewì ní ilẹ̀ Yorùbá? |
Kò dára kí àwọn ọmọdé máa bá ara wọn jà ní ìgboro. |
Níbo lẹ ti rí Yorùbá lókè ọya tó ń gun ẹṣin? |
Ìtúnu ààwẹ̀ máa bẹ̀rẹ̀ ní ọ̀túnla, mo sì máa lọ sí abúlé wa. |
Wọ́n ṣe ètò ìpàdé ìta gbangba ní àwọn àgbègbè kọ̀ọ̀kan. |
Ẹgbẹ́ aṣòfin ilẹ̀ yìí ní ìjọba ń tẹ ẹ̀tọ́ olùdíje ààrẹ́ tẹ́lẹ́ náà lóju |
Àwọn aláìníkanṣe ló ń pè fún ìyapa Nàìjíríà ni Gómìnà Oyètọ́lá sọ |
Àwọn ọ̀dọ́ yarí pé àwọn ni ìjọba tọsí. |
Ọba tó fẹ́ jẹ kò ṣe àwọn ètùtù tó yẹ kí ó ṣe rárá. |
Ìṣẹ̀lẹ̀ náà tó wáyé ní lóṣù Keje, ọdún yìí. |
Aláàfin ní onílù òun ló ń tú àṣírí ìkà ènìyàn. |
Ọmọ Yorùbá sọ fún olorì pé kò yẹ kó tú àṣírí ìkọ̀kọ̀ ìgbéyàwó rẹ. |
Rẹ̀mí bẹ ilé ẹjọ́ láti gbà òun láàyè kó gbé Ìgbòho. |
O ti pẹ́ tí Ẹgbẹ́ Alákùkọ ti ń dìbò yan mọ̀lẹ́bí Túndé Ọlọ́kọ̀ |
Ààrẹ wa Adébáyọ̀ ti kọ̀wé fipo silẹ̀ nítorí rògbòdìyàn tó ń ṣẹlẹ̀. |
Ìgbòho wà lọ́nà IÌbàràpá. |
Kò ní dára kí ọkùnrin máa fi ẹnu lásán bá obìnrin sọ̀rọ̀ |
Ìjọba ìlú Èkó ní kọ́ yọ ilé náà kúrò pátápátá. |
Gómìnà ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun ní àsìkò ti tó kí ará ìlú lọ ra ìbọn tiwọn |
Àpò kan ní owó oṣù àkọ́kọ́ mi nìdí iṣẹ́ tíátà. |
Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ mẹ́fà lára àwọn tó le ní ọgọ́rùn tí wọ́n jí gbé |
Báyìí ni ẹgbẹ́ ajàfẹ́tọmọnìyàn sọ pé ikú ló tọ́ sí apanìyàn. |
Mo pàdé àwọn ọmọ òrukàn méje kan lọ́nà Abẹ́òkuta. |
Lọ kà nípa àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ ewu tó ṣẹlẹ̀ ní ìlú ẹ̀kọ́ |
Afẹ́nifẹ́re àti Ọmọ Oòduà ti fún Adesina lésì ọ̀rọ̀ tó sọ níjẹta. |
Ṣèyí Mákindé ti gba ẹgbẹ́ mìírà lọ o, kílódé? |
Àlùfáà dí ọkọ lọ́wọ́ láti máṣe gun aya rẹ̀ ní ọ̀bẹ. |
Ọ̀jọ̀gbọ́n ní àwọn òbí ayé òde òní kò ṣiṣẹ wọn bí iṣẹ́ lórí ọmọ |
Subsets and Splits
No community queries yet
The top public SQL queries from the community will appear here once available.