audio audioduration (s) 2.05 19.2 | text stringlengths 16 191 | speaker_id int64 1 3 |
|---|---|---|
Ṣe ni obìnrin yìí kọ́kọ́ ń bá a sọ̀rọ̀ o. | 1 | |
ohun tó máa sọ bí ìgbésí ayé rẹ ṣe máa láyọ̀ tó ní báyìí àti lọ́jọ́ iwájú. | 1 | |
(Òwe 518, 19) A mọ̀ pé ọ̀rọ̀ ìbálòpọ̀ sábà máa ń wá séèyàn lọ́kàn gan-an, pàápàá nígbà tó bá ṣì wà lọ́dọ̀ọ́. | 1 | |
Àwọn wọ̀nyí á máa wọlé sáwọn ọmọdé lára díẹ̀díẹ̀ nípa dídọ́gbọ́n mú ọ̀rọ̀ ìbálòpọ̀ wọ inú ìjíròrò wọn wẹ́rẹ́wẹ́rẹ́. Ṣó Léwu Láti Máa Sọ̀rọ̀ Ìbálòpọ̀ Lórí Íńtánẹ́ẹ̀tì? | 1 | |
àwọn nǹkan tó ń ṣẹlẹ̀ láwùjọ, olùkọ́ wọn sì máa ń mójú tó wọn. | 1 | |
Àwọn ilé ìwé kan ti ń lò ó báyìí láti ráàyè bá àwọn èèyàn sọ̀rọ̀ ní orílẹ̀-èdè míì. | 1 | |
Àwọn ibi ìfọ̀rọ̀wérọ̀ kan wà lórí Íńtánẹ́ẹ̀tì tó máa ń wu àwọn ọ̀dọ́ jù láti lọ. | 1 | |
Ẹnì kan wà tó ní ọrọ̀, ọgbọ́n àti agbára láti lè yanjú wàhálà ilégbèé tó ń ṣẹlẹ̀ lọ́wọ́lọ́wọ́. | 1 | |
Bí àpẹẹrẹ, àtẹ̀jáde kan láti ilé iṣẹ́ ọ̀tẹlẹ̀múyẹ́ ilẹ̀ Amẹ́ríkà, ìyẹn Federal Bureau of Investigation, kìlọ̀ nípa àwọn kan tó máa ń tètè dá ọ̀rọ̀ ìbálòpọ̀ sílẹ̀ tí wọ́n á | 1 | |
Ìṣòro àwọn abọ́mọdé-ṣèṣekúṣe pọ̀ gan-an lórí Íńtánẹ́ẹ̀tì débi táwọn ìjọba fi ní ìlànà lórí bá a ṣe lè dáàbò bo àwọn ọ̀dọ́. | 1 | |
Àwọn Oníṣekúṣe Máa Ń Dọdẹ Àwọn Ọmọdé Níbẹ̀ Abigail sọ pé | 1 | |
Kódà, àwọn ọmọ ilé ẹ̀kọ́ kan lè bá onímọ̀ iṣẹ́ ẹ̀rọ, oníṣègùn tàbí akọ́ṣẹ́mọṣẹ́ míì fọ̀rọ̀ wérọ̀ nípa iṣẹ́ ilé ẹ̀kọ́ wọn. | 1 | |
Kí ló lè mú káwọn olóṣèlú káàkiri àgbáyé àti lórílẹ̀-èdè kọ̀ọ̀kan pa ìmọtara-ẹni-nìkan tì kí wọ́n sì fìmọ̀ ṣọ̀kan láti wá ojútùú sí ìṣòro gbogbo àwọn tíyà ń jẹ? | 1 | |
gbogbo àwọn tọ́ràn kàn [á lè] borí ìwà ọ̀dájú wọn, táwọn olóṣèlú á sì ní ìfẹ́ láti ran àwọn èèyàn bíi tiwọn lọ́wọ́, torí pé ohun tí kò jẹ́ káwọn | 1 | |
Bí àpẹẹrẹ, nígbà tí wọ́n fọ̀rọ̀ wá ọ̀rọ̀ wò lẹ́nu àwọn ọmọ ilé ẹ̀kọ́ gíga kan ní Gúúsù ilẹ̀ Amẹ́ríkà, wọ́n rí i pé èyí tó pọ̀ jù lọ lára | 1 | |
Ó bi mí pé, ‘Bá a bá ń bára wa jáde láìjẹ́ káwọn òbí ẹ mọ̀ ńkọ́?’ Àmọ́ ṣá o, Bíbélì pàṣẹ pé kó o máa gbọ́ràn sáwọn òbí ẹ | 1 | |
Mo ṣàlàyé fún un pé ọ̀kan lára àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ni mí, mi ò sì ní lè máa bá ẹni tí kì í ṣe Ẹlẹ́rìí Jèhófà bíi tèmi jáde. | 1 | |
Kí ló wá yẹ kí wọ́n ṣe tí wọn ò tíì ṣe? | 1 | |
ìṣòro àwọn tó ń gbé inú ebútú. | 1 | |
Bẹ́ẹ̀ sì rèé, àwọn wọ̀nyí kì í ṣọ̀lẹ o, wọn kì í sì í ṣe alápámáṣiṣẹ́. | 1 | |
Láàárín ogún ọdún sí ogójì ọdún lọjọ́ orí àwọn bí ọ̀kẹ́ méjì èèyàn tó ń gbébẹ̀ wà. | 1 | |
Àwọn ilé ebútú tí wọ́n fi amọ̀, igi àti páànù kọ́ yìí tóbi tó mítà mẹ́rin tàbí ogójì ẹsẹ̀ bàtà níbùú lóòró. | 1 | |
Téèyàn bá gba Ọ̀nà Ọgbà Gigiri, tó wà ní abúlé náà kọjá, èèyàn á rí ẹ̀rí pé táráyé bá pawọ́ pọ̀ tí wọ́n sì náwó sí i dáadáa, wọ́n á | 1 | |
Wọ́n dá abúlé yìí sílẹ̀ láti fi hàn pé àjọ àgbáyé yìí múra tán láti yanjú ìṣòro ilégbèé jákèjádò ayé. | 1 | |
Abúlé yìí, tó ń jẹ́ Gigiri, tí wọ́n mọ odi yí po, ni oríléeṣẹ́ àjọ tó ń ṣètò ilégbèé lábẹ́ àsíá Àjọ Ìparapọ̀ Orílẹ̀-èdè wà. | 1 | |
Lọ́dọọdún àràádọ́ta ọmọ ni wọ́n ń bí sínú ìṣẹ́ tó túbọ̀ ń ṣẹ́ àwọn èèyàn yìí. | 1 | |
Ó ṣe tán, títì tó wà létí ibẹ̀ tí wọ́n fẹ́ fẹ̀ sẹ́yìn máa gba orí ilẹ̀ tí ilé náà wà kọjá. | 1 | |
Kódà, ibi tí obìnrin yìí pè nílé yẹn kì í ṣe tiẹ̀ gan-an. | 1 | |
Ọ̀dọ́bìnrin kan tiẹ̀ wà níbẹ̀ táwọn ọkùnrin tó ń bá a sùn lé ní ọgọ́rùn-ún, ó wá ń ṣe fọ́ńté pé | 1 | |
Wọ́n lérò pé bí ṣíṣe eré kọ̀ǹpútà láṣejù bá ti kó sí èèyàn lórí tán, ó lè mú kí èròjà dopamine tó ń tú dà sínú ọpọlọ ẹni tó bá | 1 | |
Òun ni aṣáájú ẹgbẹ́ tó ń ṣèwádìí lórí àwọn nǹkan táwọn èèyàn ń sọ di bárakú nílé ẹ̀kọ́ gíga Charité University Hospital, nílùú Berlin, lórílẹ̀-èdè Jámánì. | 1 | |
Bí ọpọlọ àwọn èèyàn tó ń ṣe eré kọ̀ǹpútà láṣejù ṣe ń ṣiṣẹ́ jọ tàwọn ọ̀mùtí tàbí tàwọn amugbó. Ọ̀gbẹ́ni Ralf Thalemann tó jẹ́ afìṣemọ̀rònú ló sọ̀rọ̀ yìí. | 1 | |
pé bí ìṣòro ẹ ṣe rí gan-an ni wọ́n sọ, pé ó ní láti jẹ́ pé lóòótọ́ ní nǹkan ń ṣe ẹ́! | 1 | |
torí pé wọn ò ní àwọn ohun kòṣeémáàní, irú bí ilé gbígbé àti ètò ìlera tó péye. | 1 | |
Ìwádìí fi hàn pé àwọn òbí kan wà tí wọ́n jẹ́ onífẹ̀ẹ́, ṣùgbọ́n tí wọn ò gbàgbàkugbà, ìyẹn ni pé wọn kì í fọ̀rọ̀ àwọn ọmọ wọn ṣeré, síbẹ̀ wọn | 1 | |
lórúkọ jẹ́ láìsọ ẹyọ ọ̀rọ̀ kan ṣoṣo. | 1 | |
Gbogbo àwọn tó bá wà nípò láti máa tọ́jú ọmọ náà, tó fi mọ́ àwọn tó jẹ́ ọkùnrin lára wọn, ì báà jẹ́ bàbá ẹ̀, ọkọ ìyá ẹ̀, tàbí ìbátan | 1 | |
Bírú ìbéèrè bẹ́ẹ̀ bá tètè máa ń já ọmọ ẹ láyà, o lè gbìyànjú láti sọ ìtàn kan fún un nípa ọmọ mìíràn. | 1 | |
rò pé nǹkan míì wà tí ì bá dára jù pé kó o ṣe? O lè lo àwọn ìbéèrè míì bẹ́ẹ̀ yẹn láti fi wádìí ohun tọ́mọ kan máa rò | 1 | |
Àbí wàá fiṣẹ́ ẹ silẹ̀, tíwọ àtìdílé ẹ, àtàwọn ọ̀rẹ́ ẹ á sì máa gbádùn ara yín? | 1 | |
bẹ́ẹ̀ ní báyìí, ó dára kó o gbé àwọn ohun tó wà nísàlẹ̀ yìí yẹ̀ wò | 1 | |
Káwọn kan lára wọn bàa lè ṣe bíbá tí wọ́n ń bára wọn jáde ní bòókẹ́lẹ́, orí fóònù tàbí Íńtánẹ́ẹ̀tì ni wọ́n ti sábà máa ń bára wọn sọ̀rọ̀. | 1 | |
ti bẹ̀rẹ̀ sí bára wọn jáde, wọ́n sì ti ṣe ọ̀rọ̀ náà lókùú òru fáwọn òbí wọn. | 1 | |
Agbára káká lọ̀dọ́ kan lóde ìwòyí á fi sọ pé òun ò ní lẹ́ni táwọn á jọ máa jáde. Àwọn kan tọ́rọ̀ wọn rí bá a ṣe sọ tán yìí | 1 | |
Ńṣe lọ̀rọ̀ pé kí n máa bá ẹlòmíràn jáde yìí ṣáà ń gbà mí lọ́kàn débi tí mo fi máa ń ṣiyè méjì pé bóyá ni mi ò kúkú ní | 1 | |
Ó lè má rọrùn mọ́ fún ìwọ àtàwọn òbí ẹ láti jọ máa bára yín gbé. | 1 | |
Arẹ̀wà ni màmá ẹ nígbà tó wà ní kékeré bíi tìẹ! Ọ̀rọ̀ àbùkù gbáà lèyí nítorí pé ó máa mú kó o bẹ̀rẹ̀ sí í ṣe kàyéfì bóyá òburẹ́wà ni | 1 | |
ni yóò máa ronú pé àwọn ìṣòro kan wà tí àwọn ní, àmọ́ tí kò lè yanjú, irú bí ìṣòro àyíká tó dọ̀tí, àìsí omi tó mọ́ tónítóní àtàwọn ìṣòro | 1 | |
Bó bá tiẹ̀ dá bíi pé ìdánilẹ́kọ̀ọ́ náà ye ọmọ kan dáadáa, ó lè tètè gbàgbé ẹ̀ láàárín ọ̀sẹ̀ tàbí oṣù díẹ̀. | 1 | |
Èyí á jẹ́ kó lè nígboyà láti lọgun pé òun ò fẹ́rú ẹ̀, á lè tètè sá kúrò níbẹ̀, á sì lè tètè fẹjọ́ ohun tó ṣẹlẹ̀ sùn ẹ́. | 1 | |
Síbẹ̀, nípa kíkọbi ara sí ìmọ̀ràn inú Bíbélì, irú ẹni bẹ́ẹ̀ lè pinnu pé òun ò ní mú irú ìfẹ́ ọkàn bẹ́ẹ̀ ṣẹ. | 1 | |
Ṣé èyí wá túmọ̀ sí pé ìbínú ò tún ní ru sókè nínú ẹ̀ mọ́ láé? | 1 | |
Ẹnì kan lè jẹ́ ẹni tó máa ń fi ara [ẹ̀] fún ìhónú. Kírú ẹni bẹ́ẹ̀ tó kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì, ó lè jẹ́ pé kọ́rọ̀ tó ṣe bí ọ̀rọ̀ pẹ́rẹ́n ló | 1 | |
pàápàá ẹnì kan tẹ́ ẹ jọ sún mọ́ra, ìyẹn lè mú kó o máa jowú onítọ̀hún kó o sì máa bínú sí i. Mia mọ bó ṣe máa ń rí | 1 | |
Ẹnì kan tó ń jẹ́ April náà tún ṣàlàyé ìdí míì tí irú àfiwé bẹ́ẹ̀ fi lè bani nínú jẹ́, ó sọ pé, báwọn èèyàn bá fi ẹ́ wé ẹlòmíì, | 1 | |
Ìwé ìròyìn Time sọ pé láti kékeré làwọn èèyàn tó wà níbẹ̀ ti máa ń ní ìbálòpọ̀, wọn kì í sì í fi mọ sọ́dọ̀ ẹnì kan ṣoṣo. | 1 | |
Bó bá jẹ́ pé ohun táwọn èèyàn bá ṣáà ti fẹ́ ló kù tí wọ́n ń hù níwà báyìí, láìsí ìlànà kankan tí wọ́n á gbé ìwà wọn kà láti | 1 | |
Afẹ́fẹ́ ọ́síjìn, ìyẹn afẹ́fẹ́ tó ń gbẹ́mìí ró ò ní tó mọ́ nínú ọpọlọ, wàá sì dákú. | 1 | |
ń lọ káàkiri inú ara bó ṣe yẹ yìí ò bá ṣiṣẹ́ dáadáa mọ́, ó di dandan kéèyàn dákú, bíi nígbà tẹ́ni tó wà lórí ìjókòó tẹ́lẹ̀ bá dédé dìde | 1 | |
tí ọrọ̀ ti ṣe fáwọn jù lọ ni pé ó máa ń mú inú bí àwọn. Lẹ́nu àìpẹ́ yìí, àwọn ògbógi tó lé ní ọgọ́rùn-ún láti orílẹ̀-èdè mẹ́rìnlá pàdé nílùú | 1 | |
jù lára àwọn milọníà náà ni wọ́n nífẹ̀ẹ́ owó tí wọ́n sì tún kórìíra ẹ̀. Ọ̀pọ̀ lára àwọn tó kópa nínú ìwádìí náà sọ pé bá a bá yọwọ́ pé | 1 | |
Ìyẹn á wá mú kí eré náà túbọ̀ máa gbádùn mọ́ ọn títí tá á fi di bárakú. Lẹ́yìn táwọn kan ṣèwádìí, wọ́n tiẹ̀ dámọ̀ràn pé èyí lè ṣẹlẹ̀ sí | 1 | |
ń ṣeré kọ̀ǹpútà náà máa pọ̀ sí i. | 1 | |
gba tèmi náà.’ Kí ló máa ń mú kéèyàn ronú pé òun ò dáa tó àwọn míì ná? | 1 | |
Ọ̀kan lára ìdí tí àfiwé fi máa ń dun èèyàn nígbà míì ni pé ó máa ń ta èèyàn lára. | 1 | |
Kí lo lè ṣe báwọn èèyàn bá ń fi ẹ́ wé àwọn ẹlòmíì? | 1 | |
Ṣó ní oore èyíkéyìí tírú nǹkan bẹ́ẹ̀ máa ń ṣe fúnni? | 1 | |
fọwọ́ kan ibẹ̀. Àwọn òbí méjèèjì ni wọ́n máa ń dígbà bá ọmọ náà sọ̀rọ̀ yìí, wọ́n sì máa ń fi í lọ́kàn balẹ̀ pé gbogbo ìgbà tí ẹnikẹ́ni bá | 1 | |
Bó bá sì ṣẹlẹ̀ pé wọ́n bá ọmọdé kan ṣèṣekúṣe, báwọn òbí ò bá ṣáà ti ka ọmọ náà sí onírọ́ tí wọn ò sì jáwọ́ lọ́rọ̀ ẹ̀, ó máa | 1 | |
ìbéèrè wá a lẹ́nu wò.b Bó bá sọ pé òun ò fẹ́ kẹ́ni tẹ́ ẹ ni kó máa wá dúró ti òun nílé wá mọ́, bi í pé kí nìdí | 1 | |
Ògbógi kan tó jẹ́ oníṣègùn ọpọlọ tó sì ti fi ọdún mẹ́tàlélọ́gbọ̀n tọ́jú onírúurú èèyàn tí wọ́n bá ṣèṣekúṣe sọ pé àìmọye irú ìṣekúṣe bẹ́ẹ̀ ni kì bá tí wáyé | 1 | |
Mọ gbogbo bí wọ́n ṣe fẹ́ rìn bó bá ṣẹlẹ̀ pé ilé ẹ̀kọ́ fẹ́ kó wọn rìnrìn àjò lọ síbì kan. | 1 | |
Má ṣe dá ọmọ ẹ dá gbogbo ohun tó bá ń ṣe, mọ àwọn tó ń bá ṣọ̀rẹ́, máa bá a dá sí iṣẹ́ tí wọ́n bá gbé fún un | 1 | |
yìí ṣe fi àbámọ̀ ṣáájú ọ̀ràn. | 1 | |
Nígbà tí ẹnì kan wá ń kọ́ ọ̀kan lára àwọn ọmọ wọn ọkùnrin lórin nílé, Melissa sọ fún olùkọ́ náà pé | 1 | |
Òbí tó ṣì ń tọ́ ọmọkùnrin mẹ́ta lọ́wọ́ ni Títí àti Dàmọ́lá, àmọ́ ọwọ́ kékeré kọ́ ni wọ́n fi mú ọ̀ràn jíjẹ́ kí ọmọ wọn máa dá wà pẹ̀lú àgbàlagbà. | 1 | |
Ìwà tó burú jáì ni fáwọn èèyàn kan láti máa wá àwọn ọmọdé tí wọ́n á bá ṣèṣekúṣe kiri. | 1 | |
Ìṣòro tó ń muni lómi gbáà lọ̀rọ̀ ìbọ́mọdé-ṣèṣekúṣe. | 1 | |
ara wọn tí wọ́n á sì jẹ́ aláìní ìfẹ́ni àdánidá.—2 Tímótì 31-5. | 1 | |
Ọ̀dájú ni bàbá mi, ọ̀mùtípara ni, ó sì máa ń tètè fara ya. | 1 | |
Wọ́n fẹ́ láti dáàbò bo ọmọ wọn lọ́wọ́ àwọn tó ń bọ́mọdé ṣèṣekúṣe. | 1 | |
Èyí tó gba Fẹ́mi àti Dúpẹ́ lọ́kàn jù lọ lára ojúṣe wọn gẹ́gẹ́ bí òbí rèé | 1 | |
ó lè kó àárẹ̀ bá ọpọlọ, ó lè máa kóni láyà sókè, ó sì lè máa múni ṣàárẹ̀. | 1 | |
Lẹ́nu àìpẹ́ yìí, wọ́n ti bẹ̀rẹ̀ sí í ki àwọn èèyàn nílọ̀ nínú àwọn ìwé, nínú onírúurú àpilẹ̀kọ, nínú àwọn ètò orí tẹlifíṣọ̀n àti eré sinimá pé kí wọ́n yé | 1 | |
kò sígbà kankan tó burú pé kó wá fi ẹjọ́ onítọ̀hún sun ẹ̀yin tẹ́ ẹ jẹ́ òbí rẹ̀. | 1 | |
Bí ẹnikẹ́ni bá sọ fún ẹ pé kó o ṣe ohun tí Jèhófà Ọlọ́run sọ pé ó burú, o ò gbọ́dọ̀ ṣe é o. | 1 | |
Bó tilẹ̀ jẹ́ pé ìyẹn lè dún bí ohun tó ṣòroó ṣe, lójú àwa tá a jẹ́ Kristẹni ohun tó rọrùn gbáà ni. | 1 | |
Àwọn abọ́mọdé-ṣèṣekúṣe tètè máa ń kíyè sí àwọn ọmọdé tí wọ́n bá máa ń yára ṣègbọràn jù. | 1 | |
Àwọn ògbógi nípa ìtọ́jú ọmọ àti béèyàn ṣe lè dènà ìbọ́mọdé ṣèṣekúṣe dábàá pé káwọn òbí máa báwọn ọmọ wọn sọ irú ọ̀rọ̀ yìí. | 1 | |
fọwọ́ kàn án níbi tí kò yẹ tàbí tí wọ́n bá ṣe ohun tó ni ín lára ni kó máa wá sọ fáwọn. | 1 | |
ń kúrò lójú ajọ̀, àwọn òbí tó ń dá tọ́mọ sì ń pọ̀ sí i. Ìwà rere ti ń kógbá sílé lórílẹ̀-èdè Ṣáínà náà. | 1 | |
Níbi Àpérò Àwọn Ìyá Lórílẹ̀-Èdè Nàìjíríà, tó jẹ́ àkọ́kọ́ irú rẹ̀ tó wáyé, ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà sọ ẹ̀dùn ọkàn rẹ̀ nípa ibi tí orílẹ̀-èdè náà ń dorí kọ. | 1 | |
láti gbé àìlóǹkà òfin kalẹ̀ nítorí àtikiwọ́ ìwà ọ̀daràn bọlẹ̀. | 1 | |
fi pinnu bóyá ó tọ́ tàbí kò tọ́, a jẹ́ pé ó di dandan kí òfin wà táá máa yẹ̀ wọ́n lọ́wọ́ wò. —Ọ̀MỌ̀WÉ DANIEL CALLAHAN. | 1 | |
lọ sínú ọpọlọ ló máa ń mú kéèyàn dákú. | 1 | |
Lẹ́yìn témi àti dókítà kan tó láàánú lójú ti sọ̀rọ̀ nípa rẹ̀, témi náà sì ti ṣèwádìí nínú àwọn ìwé mélòó kan, mo rí i pé àìtó ẹ̀jẹ̀ tó ń | 1 | |
Ìyẹn ò fi bẹ́ẹ̀ dáa tó ṣá o. | 1 | |
Gẹ́gẹ́ bí ìròyìn kan láti orílẹ̀-èdè Kánádà ṣe fi hàn, bá a bá kó ọgọ́rùn-ún èèyàn bí irú tèmi jọ, nǹkan bíi mẹ́ta lára wa sábà máa ń dákú bí | 1 | |
Ńṣe ni mo máa ń dákú. | 1 | |
Èmi fúnra mi ti mọ ohun tó máa ṣẹlẹ̀ bó bá ṣe bẹ́ẹ̀. | 1 |
End of preview. Expand in Data Studio
README.md exists but content is empty.
- Downloads last month
- 75