Dataset Viewer
Auto-converted to Parquet Duplicate
audio
audioduration (s)
2.05
17.6
text
stringlengths
17
190
speaker_id
int64
3
3
Àmọ́ ṣá, pé oríṣiríṣi làwọn ọkùnrin tó ń lu ìyàwó wọn yìí kò túmọ̀ sí pé àwọn ọ̀nà kan wà tí wọ́n ń gbà ṣe é tí kò burú o.
3
Ohun kan tó sábà máa ń fa àìróorunsùn fún àwọn àgbàlagbà jẹ mọ́ híhan-anrun.
3
Ìdí nìyẹn tó fi jẹ́ pé ìwọ̀n mítà tí wọ́n ń pè ní nanometer ni wọ́n máa ń fi wọn fullerenes torí bó ṣe kéré tó.
3
Tó o bá fara balẹ̀ gbọ́ ti ẹnì kejì rẹ, tí o kò sì já ọ̀rọ̀ gba mọ́ ọn lẹ́nu, ìyẹn máa tètè paná ìbínú, á sì mú kí ẹ
3
Kódà, níbi tí ara bá tu onítọ̀hún dé, kò tiẹ̀ ní fẹ́ dìde lórí ibùsùn ní òwúrọ̀ ọjọ́ kejì.
3
Bí èròjà yìí kò bá tó nínú ẹ̀jẹ̀ rẹ̀—èyí tó máa ń ṣẹlẹ̀ sí ọ̀pọ̀ àwọn obìnrin láwọn orílẹ̀-èdè tó ṣẹ̀ṣẹ̀ ń gòkè àgbà—ó lè yọrí sí àìsàn.
3
Oríṣiríṣi nǹkan làwọn èèyàn máa ń sọ nípa fífi àwọn àwòrán tàbí ọ̀rọ̀ tó ń mọ́kàn ẹni fà sí ìbálòpọ̀ ránṣẹ́ lórí fóònù.
3
èròjà protein náà tí á sì gbógun tì í.
3
Gbìyànjú Láti Borí Ìkórìíra Nípa Níní Ìjìnlẹ̀ Òye Ńṣe ni Michael, tí a mẹ́nu kàn níṣàájú, pẹ̀lú ṣèkáwọ́ inú tó ń bí i, bí bẹ́ẹ̀ kọ́, ì bá ṣòro gan-an
3
Bó O Ṣe Lè Fi Ọ̀wọ̀ Hàn Ọkọ sọ pé
3
Ó lè yà ẹ́ lẹ́nu lóòótọ́, àgàgà tó o bá wà lára àwọn tó gbà pé ọkùnrin ló yẹ kó dẹnu kọ obìnrin.
3
Bákan náà, àwọn ìṣòro kan wà téèyàn ò retí tó lè fayé ni tọkọtaya lára, irú bí ọ̀rọ̀ owó tàbí ìtọ́jú ẹnì kan tó ń ṣàìsàn tó le gan-an nínú
3
Máa yẹra fún àwọn kòkòrò tó máa ń kó àrùn ranni.
3
Àjọ Ìparapọ̀ Àwọn Orílẹ̀-Èdè Lórí Ètò Ẹ̀kọ́, Ìmọ̀ Ìjìnlẹ̀, àti Àṣà Ìbílẹ̀ [UNESCO] sọ pé
3
mìíràn nílò oorun tó tó wákàtí mẹ́wàá.
3
Ìtọ́sọ́nà tó o nílò wà nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run.
3
Alágbèéká. Yàtọ̀ sí pé tẹlifóònù yìí máa ń jẹ́ kí wọ́n já lu ohun téèyàn bá ń ṣe, wọ́n tún lè dá họ́wùhọ́wù sílẹ̀ ní pópó nítorí rírí téèyàn máa
3
Wọ́n tilẹ̀ lè ṣàlàyé ọ̀rọ̀ náà fún ọ, kí wọ́n sì tún fún ọ ní àwọn ìdánilójú tí o nílò.
3
Àpilẹ̀kọ wa tó gbẹ̀yìn máa dáhùn àwọn ìbéèrè wọ̀nyí.
3
Àmọ́, wọ́n ba mẹ́sàn-án jẹ́ nínú àwọn igi mẹ́wàá tí kò sí ilé oyin lára wọn.
3
dá yánpọnyánrin sílẹ̀ nínú ìdè ìgbéyàwó?—Ọ̀mọ̀wé Nina S.
3
tẹbí tọ̀rẹ́ máa gba tẹni rò, kó máà sí ìjà kó máà sí ìta, kéèyàn sì máa fọwọ́ pàtàkì mú ọ̀ràn ẹ̀sìn.
3
Oríṣiríṣi ẹ̀sìn àwọn ará Áfíríkà tí wọ́n yí padà ni wọ́n wá mú wọnú ẹ̀sìn Kristẹni. Irú bẹ́ẹ̀ ni ti ayẹyẹ tí wọ́n ń ṣe fún Benedict, tó jẹ́ ọ̀kan
3
Ó ń gba tèèyàn rò, ó sì lójú àánú.
3
Bí wọ́n bá gbìyànjú láti sá lọ, àlùpamáàkú ni.
3
Ìdáhùn rẹ sí àwọn ìbéèrè bí irú ìwọ̀nyí lè sọ ọ̀pọ̀ nǹkan nípa bí ààbò ṣe wà fún ọ tó níbi iṣẹ́ rẹ.
3
Má ṣe ronú pé ńṣe lẹ́nì kejì rẹ fẹ́ mọ̀ọ́mọ̀ ṣe ohun tó dùn ẹ́, rántí pé aláìpé lòun náà.
3
Àwọn aládùúgbò mọrírì ìrànlọ́wọ́ yìí gan-an ni, ẹnu sì yà wọ́n bí wọn ò ṣe béèrè kọ́bọ̀ lọ́wọ́ wọn.
3
Ká sọ pé ọkọ tàbí aya ẹ ń dá ẹ lẹ́bi lórí nǹkan kan ńkọ́?
3
Ọ̀ràn gbígbìyànjú láti mú kí ìgbéyàwó wa gún régé ti sú mi.
3
Àwọn Ìwà Rere Tó Ń Mú Káyé Ẹni Dára Christina kọ́kọ́ rò pé àlá lòun ń lá!
3
Báwo lo ṣe wá lè sá fún irú àwọn èèyàn tí Bíbélì pè ní àwọn asọ̀rọ̀ tí kò lérè àti àwọn tí ń tan èrò inú jẹ Gbàrà tí o
3
Ó ní ó wu òun kẹ́ ẹ máa fẹ́ra àti pé òun fẹ́ mọ̀ bóyá bó ṣe ń ṣe ìwọ náà nìyẹn.
3
Ọ̀rọ̀ yìí gbàrònú gidi, àbí bẹ́ẹ̀ kọ́?
3
Mo kà á sí iṣẹ́ ọpọlọ tó sì ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ àǹfààní láti mú káwọn mìíràn ṣe dáadáa.
3
Àmọ́, àwọn ọ̀mọ̀ràn nínú ìṣègùn gbà pé ó láwọn ohun kan tí wọ́n fi lè mọ̀, tó sì jẹ́ pé àwọn èèyàn tó pọ̀ jù lọ lọ̀rọ̀ rí bẹ́ẹ̀ fún.
3
Kò sí bí ọkùnrin tàbí obìnrin tó jẹ́ aláìpé ṣe lè mọ̀ ọ́n ṣe tó kí àwọn kùdìẹ̀ kudiẹ bíi mélòó kan má máa jẹ yọ nínú ìgbéyàwó rẹ̀ lẹ́ẹ̀kọ̀ọ̀kan.
3
Nítorí náà, kò sẹ́ni tó wà nílé nínú àwọn méjèèjì lákòókò tí iléeṣẹ́ náà bú gbàù.
3
Àmọ́ àwọn oúnjẹ tó sábà máa ń gbòdì lára ni àwọn oúnjẹ kéékèèké bíi mílíìkì, ẹyin, ẹja, edé, alákàn, ẹ̀pà, ẹ̀wà sóyà, ẹ̀pà inú èso àti wíìtì.
3
Ó wá di bó ò lọ o yà fún mi lójú pópó.
3
Kí ló mú kí àjọṣe àrà ọ̀tọ̀ yìí ṣeé ṣe, kó sì yọrí sí rere?
3
Tí ọmọ rẹ bá ti ń pẹ́ jù nídìí Íńtánẹ́ẹ̀tì, sọ fún un pé ìgbà báyìí-báyìí lo fẹ́ kó máa kúrò nídìí Íńtánẹ́ẹ̀tì, kódà o lè máa wo aago fún
3
Ó níṣẹ́ tí tòmátì ń ṣe lára.
3
Kí ló mú kí awọ ejò yi tó bẹ́ẹ̀?
3
Ní ti gidi, kò sóhun tó ń jẹ́ líluni lọ́nà tó dára. Nígbà náà, kí ló lè wá mú kí ọkùnrin kan máa lu obìnrin tó jẹ́jẹ̀ẹ́ pé òun á
3
àti tàwọn ẹlòmíràn ní orílẹ̀-èdè Ísírẹ́lì, àti bí àwọn èèyàn kan ṣe máa ń ṣíná ìbọn bolẹ̀ láìbìkítà láwọn ibòmíràn.
3
Àbí ó ń jowú wọn ni?
3
Mo mọ̀ pé nígbà tí ẹni tó ń ṣọ́ wa náà wá mọ irú ẹni tí a jẹ́, ó wá rí i pé kò dáa bí òun ṣe ń fipá
3
Awalẹ̀pìtàn, Zahi Hawass, ààrẹ Àjọ Tó Ga Jù Lọ Lórí Ọ̀rọ̀ Ohun Ìṣẹ̀ǹbáyé ní Íjíbítì sọ pé
3
Ní ọwọ́ mìíràn ẹ̀wẹ̀, àwọn kan tó ń jí èèyàn gbé máa ń lo ẹni tí wọ́n jí gbé láti jẹ́ kí àwọn ará ìlú lè mọ̀ nípa wọn, kí
3
pé ò ń jókòó sójú kan nìyẹn.
3
Lóòótọ́, ó lè dà bíi pé ìwọ gangan ló kọ̀ sílẹ̀.
3
Àwọn akọ́ṣẹ́mọṣẹ́ oníṣègùn máa ń ṣe àwọn àyẹ̀wò kan lórí ìlera ẹni láti mọ ohun tó ń fa àìróorunsùn àti bí wọ́n ṣe lè wò ó sàn.—Wo àpótí tó wà
3
Ǹjẹ́ bẹ́ẹ̀ náà ni ojútùú ìṣòro náà pọ̀?
3
Tó bá jẹ́ bẹ́ẹ̀, àwọn ìmọ̀ràn Bíbélì lè ràn ẹ́ lọ́wọ́.
3
Àwọn ọ̀mùnù tún máa ń hù látinú gbòǹgbò yìí láti di ìtì ọ̀gẹ̀dẹ̀ tuntun.
3
Bí kì í bá ṣe ìṣírí tó fún mi ni, mi ò ní lè gba ẹ̀bùn náà.
3
Àmọ́ ṣá o, kí àwọn oníṣègùn tó lè fún aláìsàn náà ní ìtọ́jú yíyẹ, ó ṣe pàtàkì láti mọ lájorí ohun tó ń fa ìṣòro náà gan-an.
3
Ó máa ń gbé e lọ sílé àrójẹ tó gbáfẹ́, wọ́n sì tún jọ máa ń lọ sóde àríyá.
3
Lọ́nà kan náà, ọ̀pọ̀ ló ń yan iṣẹ́ wọn kìkì nítorí iyì tí wọ́n rò pé ó ní láìro ìpalára tó ṣeé ṣe kó tibẹ̀ yọ.
3
Ohun tí James tá a fa ọ̀rọ̀ ẹ̀ yọ níbẹ̀rẹ̀ àpilẹ̀kọ yìí ṣe nìyẹn.
3
Nígbà míì, ó máa ń lo àkókò náà láti béèrè lọ́wọ́ wa bóyá a ti ń rí àwọn ọ̀dọ́ kan níléèwé tí wọ́n ń lo oògùn olóró.
3
Ǹjẹ́ a lè mú àṣà ìfiniṣẹrú kúrò pátápátá láìpẹ́?
3
Orí ìtàn kan ni fíìmù ti máa ń bẹ̀rẹ̀, èyí tó lè jẹ́ àròsọ tàbí ìrírí ayé.
3
Tí ẹni tó ta tẹ́tẹ́ bá ń ronú nípa bó ṣe máa jẹ owó, ńṣe ló ń wá káwọn míì pàdánù owó wọn, kí gbogbo owó náà lè jẹ́ tirẹ̀.
3
àwọn obìnrin kárí ayé ní ń jẹ dẹndẹ ìyà lọ́wọ́ àwọn ọkùnrin tí kò láàánú lójú.b Ọ̀pọ̀ wọn kò jẹ́ sọ iná tó ń jó wọn lábẹ́ aṣọ síta.
3
Èyí ló mú kí ọmọbìnrin náà gbẹ̀mí ara rẹ̀. Fífi àwòrán tàbí àwọn ọ̀rọ̀ tó ń mọ́kàn ẹni fà sí ìbálòpọ̀ ránṣẹ́ tún lè di ọ̀ràn òfin.
3
bá wà ní yàrá tí wọ́n ti lè máa rí àwọn igi.
3
Kò tíì pẹ́ tẹ́ ẹ ṣègbéyàwò, àmọ́ ẹ ti náwó kọjá bó ṣe yẹ.
3
Ṣíṣọ́ ohun téèyàn ń jẹ àti ohun téèyàn ń mu yóò ṣèrànwọ́ láti jẹ́ kí ara múra sílẹ̀ fún oorun amáratuni.
3
Èé ṣe tó fi yẹ kí o ka ẹni náà—tàbí àjọ tàbí ìwé náà—sí ògbógi tó ní ìmọ̀ tàbí sí ìsọfúnni tó ṣeé gbíyè lé nípa ọ̀ràn tó ń sọ?
3
Ọkọ kan tórúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Isaac sọ pé
3
wà ní ìlú ńláńlá ní ọ̀pọ̀ jù lọ àwọn orílẹ̀-èdè.
3
Jíjẹ́ ti mo tún jẹ́ òbí mú kí n nífẹ̀ẹ́ sí iṣẹ́ náà. Ohun tó sún Berthold, ọmọ ìlú Düren ní Jámánì dédìí iṣẹ́ olùkọ́ yàtọ̀ sí tàwọn tó kù
3
kò ṣeé fọwọ́ rọ́ sẹ́yìn fún ọ̀pọ̀ èèyàn.
3
Tó bá ṣeé ṣe, rí i dájú pé àdúgbò tó mọ́ tónítóní lò ń gbé, kó sì jẹ́ ibi tí wọn kò fi ìgbẹ́ tàbí ìtọ̀ bà jẹ́.
3
Púpọ̀ wọn ló ń bímọ lọ́wọ́ alẹ́ ìgbésí ayé wọn, àwọn wọ̀nyí sì sábà máa ń ko ìpèníjà títọ́jú àwọn ọmọ àti àwọn òbí pọ̀. Bó tilẹ̀ jẹ́ pé ìpín
3
bá ní èròjà folic acid tó pọ̀ tó nínú ara.
3
Ìfàjẹ̀sínilára àti Ogun Àrùn Tí Àwọn Ènìyàn Ń Kó Nínú Ẹ̀jẹ̀ Lẹ́yìn Ogun Àgbáyé Kejì, ìtẹ̀síwájú ńláǹlà nínú iṣẹ́ ìṣègùn wá mú kí á lè ṣe àwọn iṣẹ́ abẹ táwọn
3
Àwọn eré tó bá ní nǹkan àrà ọ̀tọ̀ nínú ni wọ́n máa ń gbé jáde.
3
abọ́ àdému kan tí ò ní dá ooru púpọ̀ mú un tàbí àpòòwé tó ki tó jẹ́ aláwọ̀ kakí, kó o wá fi tòmátì kan tàbí ọ̀gẹ̀dẹ̀ wẹẹrẹ kan tó
3
Èròjà carbon tó máa ń ní ihò láàárín ni wọ́n ń pè ní fullerenes.
3
Omi tó mọ́ nìkan ni kó o máa lò Àwọn ìdílé tó bá ń lo omi tó mọ́, tí wọn kò sì jẹ́ kí kòkòrò àrùn ráyè wọnú omi wọn
3
Kò yẹ kí àwọn ọmọ máa di ẹ̀bi ohun tí àwọn òbí wọn ṣe ru ara wọn. Bẹ́ẹ̀ ni, jíjẹ́ kí àwọn òbí rẹ ‘ru ẹrù ti ara wọn’ ní
3
Tó bá sì ṣẹlẹ̀ pé o kò tọ̀nà, má ṣe jẹ́ kí yẹ̀yẹ́ èyíkéyìí tí dókítà bá fi ọ ṣe dùn ọ́. Ìṣòro mìíràn tí àwọn nọ́ọ̀sì ní láti kojú
3
Láti yọ òróró ìseúnjẹ nínú àgbọn, àgbẹ̀ kan yóò la àgbọn tó ti gbó yóò sì sá a gbẹ nínú oòrùn.
3
Ta ló má bójú tó títan iná, ṣíṣe ara lóge àti ṣíṣe irun lọ́ṣọ̀ọ́?
3
Ọ̀pọ̀ nǹkan àrà ló kún ilẹ̀ ayé tá a lè kẹ́kọ̀ọ́ lára wọn bíi ti ìṣáwùrú inú òkun. Kí lèrò rẹ?
3
Ọkàn mi wá balẹ̀ dáadáa mo sì wá mọ̀wé gan-an.
3
Ara máa ń tù mí tí mo bá ti sọ bọ́rọ̀ náà ṣe rí lára mi, tí mo sì mọ̀ pé ọkọ mi fara mọ́ ohun tí mo sọ.
3
Ara fínfín kì í ṣe àṣà tuntun o.
3
bí ẹrú tàbí kí wọ́n máa gbé nínú ipò tí kò yàtọ̀ sí ti ẹrú.
3
sọ pé, mímutí nímukúmu yìí ló ń fa oríṣiríṣi àwọn àkóbá kan tó ń ṣẹlẹ̀, irú bíi jàǹbá ọkọ̀, ìwà ipá àti gbígbé májèlé jẹ, títí kan kí àwọn èwe
3
Àmọ́, ìwádìí fi hàn pé ọ̀pọ̀ àwọn tó rò pé àwọn ní ìṣòro yìí ni kò tíì ṣàyẹ̀wò nílé ìwòsàn láti mọ̀ bóyá àwọn ní in.
3
Dípò tí wàá fi jẹ́ kí àwọn nǹkan yìí kó ìrẹ̀wẹ̀sì bá ẹ, ó máa dáa kó o fara mọ́ bí nǹkan ṣe rí.— Iwájú ni kó o máa lọ.
3
Kódà bí mo bá sá kúrò nílé pàápàá, màá tún padà lọ bá a. Ohun tó máa ń já Roxana láyà ni pé ọjọ́ kan á jọ́kan tí ìwà ipá
3
Rántí pé ńṣe lo fẹ́ kí àlàáfíà jọba nínú ilé rẹ, torí náà má ṣe jẹ́ kí ara rẹ gbóná kọjá bó ṣe yẹ.
3
Ṣé torí iṣẹ́ nìkan ni mo ṣe wà láàyè, àbí torí kí n lè bójú tó ara mi ni mo ṣe ń ṣiṣẹ́?
3
Bó tilẹ̀ jẹ́ pé àwọn Kristẹni òde òní kò sí lábẹ́ Òfin Mósè, kíkà tó ka ara fínfín léèwọ̀ jẹ́ ohun tó gbàrònú.
3
Àmọ́ bí wọ́n bá ṣe é tán báyìí, gbogbo rẹ̀ á ṣe wẹ́kú, ṣe ló máa dà bíi pé ohun téèyàn ń wò ń ṣẹlẹ̀ lójú ayé ni.
3
End of preview. Expand in Data Studio
README.md exists but content is empty.
Downloads last month
76