Dataset Viewer
Auto-converted to Parquet Duplicate
id
stringlengths
5
8
speaker_id
stringclasses
8 values
text
stringlengths
4
5.29k
locale
stringclasses
1 value
gender
stringclasses
2 values
audio
audioduration (s)
3.02
580
yor_1089
2
LCC ni gigun ibori ti o gunjulo. o ni mini zoo,Ile awon Eranko ti awọn ẹranko ẹlẹwa miiran bi ijapa, ẹja, obo wa nibe
yor
Male
yor_1098
2
amala ati ewedu je ounje ti o gbajumo laarin awon omo Yoruba
yor
Male
yor_46
1
Kiìkìdá òjò àti otútù ni yóò fẹ́ ní gbogbo òru ọjọ́rú, àsìkò ti gbogbo àwọn ìyàwó ilé yóò lóyún lọ bẹẹrẹbẹ lèyìí.
yor
Female
yor_285
3
Òòrùn yóò rọra mú díẹ ní Ọjọrú nítorí ìpele òdiwọn ojú ọjọ yóò wà ní celcius mọkànlélógún sùgbọn ìdiwọn ojú ọjọ yóò yípadà láti celcius mọkànlélógún di celcius mẹsàn ti afẹfẹ yóò rọra máa fẹ. Ó ṣe é ṣe kí òòrùn ràn ní gbogbo ọsẹ.
yor
Female
yor_1789
8
Ajọ eleto idibo ipinlẹ Ondo ti ṣe akanṣe idanilẹkọọ fawọn oniroyin lẹkun Guusu Iwọ-Oorun Naijiria lori oro idibo gbogbogboo ọdun to n bọ. Idanilẹkọọ ọhun lo waye lọjọ Aje, Mọnde, ọjọ kọkandinlọgbọn, oṣu Kejila ta a wa yii ni olu ile-ẹgbẹ awọn oniroyin ipinlẹ Ondo, eyi to wa lẹyin ileesẹ to n ri sọrọ Aṣa ati eto Igbafẹ ...
yor
Male
yor_1102
2
Kini ounjẹ aarọ ti o wọpọ julọ ni owurọ satidee? ogi ati akara ni
yor
Male
yor_1227
4
Aye je okan ninu aye ti o wa
yor
Male
yor_617
5
Ghana jẹ́ ọ̀kan lára orílẹ̀dẹ̀ tí ó kéré jùlo.
yor
Female
yor_997
2
ọkunrin yi n'ka iwe iroyin
yor
Male
yor_1702
8
Obasanjo, Awolowo, Tinubu, Buhari, Dangote, Kalu, Shagari, Yar'dua
yor
Male
yor_184
1
ọdun keresi yii maa dun
yor
Female
yor_1406
6
Ofara Jo pe Ojo maaro laleyi
yor
Male
yor_1174
4
Aja n gba bóòlú
yor
Male
yor_1766
8
Ola ni odun ajinde awon omo leyin kristi
yor
Male
yor_1092
2
ounje to gbajugbaja ni ile Naijiria ni iresi
yor
Male
yor_1391
6
Kopu merin to tele ara won
yor
Male
yor_831
7
Ẹnì kọ̀ọ̀kan ló ní àǹfàní sí gbogbo ̀ẹtọ́ àti òmìnira tí a ti gbé kalẹ̀ nínú ìkéde yìí láìfi ti ọ̀rọ̀ ìyàtọ̀ ̣èyà kankan ṣe; ìyàṭò bí i ti ̣èyà ènìyàn, àẁọ, akọ-n-bábo, èdè, ẹ̀sìn, ètò ìṣèlú tàbí ìyàṭò nípa èrò ẹni, oríḷè-èdè ẹni, orírun ẹni, ohun ìní ẹni, ìbí ẹnitàbí ìyàt̀ọ mìíràn yòówù ko j̣é. Síwájú sí i, a kò g...
yor
Female
yor_1589
8
Ipele meta ati iyika olomi aro meji
yor
Male
yor_1038
2
si sọ mọkanla di pupo ni ọna áadọ́fà jẹ ẹ̀wá dín ní okòó-lé-ní-ẹgbẹ́fà
yor
Male
yor_1373
6
Ewe to gbe circle Yelo lowo
yor
Male
yor_428
3
Ọdún òmìnira ọdún yìí dùn, ó lárinrin nígbà tí ààrẹ̀ orílẹ̀-èdè kéde ẹ̀kúnwó owó oṣù tuntun fún àwọn òṣìṣẹ́.
yor
Female
yor_537
5
Òni ọjọrú, ọjọkọkànlélọgbọn òrùn yóò ràn gan, Kò sí apẹẹrẹ òjò rara, ìgbélọsókè òrùn yóò ràn ní ìlópo mèjì nì ọwò ago kan ọsán, ìgbóná ojú ọjọ yóò wà ní ìpele ogùnlémẹta, atégún yóò máa fẹ ní mẹjìlèlógún dìgírì láàrin ìséjú àayá.
yor
Female
yor_355
3
Ìjọba ìbílẹ̀ Ikorodu ni ó tóbi jùlọ nínú àwọn ìjọba ìbílẹ̀ tí ó wà ní ìlú Èkó.
yor
Female
yor_610
5
Rayfield ni àdúgbò tí ó dára fún ènìyàn láti gbẹ́ jùlọ ní ìlú Jos.
yor
Female
yor_1324
4
Olukọni ẹlẹsin Cote d'Ivoire, Emerse Fae ti sọ pe oun yoo pese ilana ti o bori fun ikọlu ẹgbẹ rẹ pẹlu Super Eagles ti Nigeria. Awọn erin yoo koju Super Eagles ni ipari idije Awọn orilẹ-ede Afirika 2023 ni papa boolu Alassanne Quattara Ebimpe, Abidjan ni ọjọ Aiku. A yoo gba ọja ni ọjọ meji to nbọ, a yoo ṣe itupalẹ Nige...
yor
Male
yor_1338
4
Ọjọ Ominira, ti a mọ ni colloquially bi Oṣu Kẹwa akọkọ, jẹ isinmi orilẹ-ede osise ni Nigeria, ti a ṣe ni Akoko ti Oṣu Kẹwa. Ó jẹ́ àmì ìkéde òmìnira ní Nàìjíríà kúrò lọ́wọ́ ìjọba ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì ní ọjọ́ kìíní oṣù kẹwàá ọdún 1960.[1] Ọdọọdun ni ijọba orilẹede Naijiria ṣe ayẹyẹ isinmi naa. Awọn ayẹyẹ bẹrẹ pẹlu adirẹsi ti Aar...
yor
Male
yor_965
7
Yoruba bọ, wọn lẹni ti ko gbọ tẹnu ẹga ni yoo sọ pe ẹyẹ oko n paato, ọga agba tẹlẹri fun banki apapọ ilẹ wa, iyẹn Central Bank of Nigeria (CBN), Alagba Godwin Emefiele, to ṣẹṣẹ jade lahaamọ ẹwọn Kuje laipẹ yii ti sọrọ lori awọn ẹsun ti wọn fi kan an, o ni irọ nla ni wọn n pa mọ oun, oun o ṣi akaunti rẹpẹtẹ sawọn banki ...
yor
Female
yor_853
7
Eko ni olú ìlú Nàìjíríà nípa eto ọrọ aje
yor
Female
yor_1258
4
Pupọ julọ awọn olokiki ni Ilu Eko ngbe ni erekusu naa
yor
Male
yor_515
5
Òrùlẹ aláwọ arọ tí ó ní àwọ funfun dóndó lórí, ààdó ayàkàtà aláwọ ewé wà ní gbogbo àyíká òrùlé náà.
yor
Female
yor_1041
2
idasimẹrin ogun jẹ marun
yor
Male
yor_388
3
Ìbàdàn. Kano. Abuja. odò Ọ̀sun-Òsogbo, Oke-olúmo, apá ìwọ̀-oòrùn orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Òkè-Láyípo. ìlú Ìdànrè. Òke-ọya. Ilé-Ifẹ̀. Odò Oguta, odo Kainji. Oke-Obudu, Òkè-Mambilla.
yor
Female
yor_813
7
Idamẹta ọgọta jẹ ogún
yor
Female
yor_123
1
Ilẹẹ̀ Yoruba ni Ìlọrin
yor
Female
yor_420
3
Ọjọ́ kìn-ní oṣù Kẹwàá ni ọjọ́ tí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà máa ń ṣe ayẹyẹ ọdún òmìnira tí a bọ́ lóko amúnisìn
yor
Female
yor_931
7
Mo fọ aṣọ ni ọjọbọ.
yor
Female
yor_1601
8
itansan orun
yor
Male
yor_1566
6
Funke Akindele (tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹrìnlélógún oṣù kẹjọ ọdún 1977) tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ń Jennifer jẹ́ òṣèrébìnrin àti olóòtú sinimá àgbéléwò ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Wọ́n bí Fúnkẹ́ sí ìlú Ìkòròdú, ní ìpínlẹ̀ Èkó lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà . Eré orí tẹlifíṣọ̀n kan tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ "I need to know" eyi ti otumo si mo ni l...
yor
Male
yor_1157
4
Adagun omi wa laarin oke
yor
Male
yor_279
3
Ní ọjọ Ìsẹgun ní agogo márùn-un ìrọlẹ gbígbóná ojú ọjọ yóò wà ní ìpele mọkànlélógún, kùrukùru yóò wà ní ìwọn márùnléláàdọta, afẹfẹ yóò máa fẹ ní kìlómítà mọkàndínlógún láàrin wákàtí kan. Kò sí àpẹẹrẹ òjò láàárín gbogbo òsè náà nítorí pé oòrùn yóò mú gidi gan-an.
yor
Female
yor_704
5
Kúrùpù (tabi laringotrakiobronkaitis) jẹ arun nipa mimi ti o lewu gan-an ti o maa nwaye nipa aisan ọ̀nà-atẹgun oke. Arun yii maa nfa wiwu ninu ọ̀nàfun. Wiwu yii maa nfa idiwọ fun mimi deede; awọn aami aisan Kúrùpù ni ikọ́ "gbígbó", idiwọ ọnafun (mimi ti o ngbọn ti ìró rẹ lọ soke), ati ohùn kíkẹ̀. Awọn aami aisan kúrùpù...
yor
Female
yor_900
7
Eba, irẹsi, dodo, Isu dundun, akara, moimoi, burẹdi, ẹwà, ọdunkun, àmàlà, ọ̀gẹ̀dẹ̀ àgbagbà ati bebelo
yor
Female
yor_1036
2
si sọ meje di pupo ni ọna mẹjọ jẹ mẹ́rìndínlọ́gọ́ta
yor
Male
yor_1688
8
Expressway1/Lagos - Ojoo Expy/E1 si Ibadan
yor
Male
yor_264
3
Àwòrán òrùlé aláwọ aró pẹlú àwọn koríko aláwọ ewé lórísìrísi
yor
Female
yor_1208
4
mọkanla ni isodipupo nipasẹ ọgọrun o le mẹwa dọgba ni egberun kan igba ati mẹwa
yor
Male
yor_40
1
Ní aago kan òru ọjọ́rú, ìrì fẹ́rẹ́fẹ́ ń sẹ̀, kò sí ooru rárá, ìrì tó ki ń sẹ̀, báyìí ni yóò ṣe rí fún gbogbo ọ̀sẹ̀ yìí
yor
Female
yor_411
3
Ishi ewu ni mo jẹ ní ibi ìnáwó Oluchi tí a lọ ní ọ̀ṣẹ̀ tí ó kọjá.
yor
Female
yor_292
3
Ojú ọjọ kò dára rárá. Ìwọn òdíwọn ojú ọjọ yóò wà ní celcius marùndínlọgọrin. Ó ṣe é ṣe kí afẹfẹ dúró sí ojú kàn gbari
yor
Female
yor_15
1
okunrin joko lori aga ijo to n kawe
yor
Female
yor_805
7
Ìdáméjì ọgọrùn jẹ àádọta
yor
Female
yor_129
1
Gomina Ipinle Ogun ni Ogbeni Dapo Abiodun.
yor
Female
yor_895
7
Ọjọ ajé ni lọ sí ọjà Bódìjà, Oja Oba ati Ọjá Gbagi.
yor
Female
yor_955
7
Ileeṣẹ aarẹ Naijiria lo ti dẹbi ipo ti ijọba awaarawa wa nilẹ yii ru aarẹ tẹlẹ ri, Olusegun Obasanjo. Oludamọran fun Aarẹ Bola Tinubu lori eto iroyin, Bayo Onanuga lo fesi fun Obasanjo lori bo ṣe juwe oṣelu awaarawa bii ohun ti ko ṣe anfaani fun ọpọ ọmọ Naijiria ati Africa lapapọ. Aarẹ tẹlẹ ri naa lo sọrọ nibi ipade ap...
yor
Female
yor_1746
8
Dodo ati eyin dindin je ounje awon alakowe
yor
Male
yor_1074
2
Muhammadu Buhari ni Aare keje lati 31,ookanlelogbon Oṣu kejila ọdun 1983 si 27 Oṣu Kẹjọ ọdun 1985
yor
Male
yor_441
3
Ṣé òótọ́ ni pé Eṣù láàlú jẹ́ ènìyàn dúdú?
yor
Female
yor_1402
6
Oju Ojo eni Oda.
yor
Male
yor_1353
4
Oṣupa fi kokoro kekere kan ranṣẹ si awọn eniyan. Ó ní, “Lọ sọ́dọ̀ àwọn ènìyàn kí o sì sọ fún wọn wipe pé, èmi yóò kú, èmi yóò sì jí dìde. Kokoro naa bẹrẹ si ni lọ, ṣugbọn ehoro kan sare soke o beere, "Nibo ni iwọ nlọ?" "Mo n lọ si odo awọn eniyan," kokoro naa sọ. "Oṣupa sọ fun mi lati sọ fun awọn eniyan wipe oun ku at...
yor
Male
yor_84
1
Aimoye goolu ninu ideje kan
yor
Female
yor_4
1
Irisi irawo laarin irisi roboto
yor
Female
yor_585
5
1.Ẹnì kọ̀ọ̀kan ló ní ẹ̀tọ́ láti jé ọmọ orílẹ̀-èdè kan. 2.A kò lè ṣàdédé gba ẹ̀tọ́ jíjé ọmọ orílé-èdè ẹni lọ́wọ́ ẹnì láìnídìí tàbí kí a kọ́ fún ẹnìkẹ́ni láti yàn láti jé ọmọ orílẹ̀-èdè mìíràn.
yor
Female
yor_1494
6
Ikeja City mall je Ibi kan to Gbajumo ni Ikeja
yor
Male
yor_468
3
https://yo.wikipedia.org/wiki/Ile-i%E1%B9%A3%E1%BA%B9_Am%E1%BA%B9rika_ti_Brasil Ile-iṣẹ Amẹrika ti Brasil ni orisun ti o jẹ pataki ti ilana isakoso faili (SIGA) ni ilu Brasil. O ṣẹda ni ojo 2 Oṣu Kinni ọdun 1838 ati pe o ni ori ile-iṣẹ rẹ ni Rio de Janeiro. Gẹgẹbi Ofin ti Ile-itọju (Ofin 8.159) ti Oṣu Keje 8, 1991, o n...
yor
Female
yor_181
1
Ọla ni awọn INEC maa pari kika ibo
yor
Female
yor_1176
4
Awon oyin meta ri ododo meta
yor
Male
yor_924
7
A nlọ Jerusalemu lọla
yor
Female
yor_1181
4
awọn oniwe owurọ ojoru, digiri mejila nibẹ ni ina drizzle
yor
Male
yor_1133
2
Ọjọ Ominira , ti a mọ ni colloquially bi Oṣu Kẹwa akọkọ October 1st , jẹ isinmi fun awon osise ni orilẹede Nigeria ,a ma n se Ni October 1st ti Oṣu Kẹwa. Ó jẹ́ àmì ìkéde òmìnira ní Nàìjíríà lọ́wọ́ ìṣàkóso ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì ní ọjọ́ kìíní oṣù kẹwàá ọdún 1960. [1]
yor
Male
yor_389
3
Orí òkè-láyípo ni a tún mọ̀ sí Bower's Tower. Òkè yìí wà ní ìlú Ìbadàn, orí òkè yìí ni àwọn ọmọ ogun Ìbadàn máa ń gùn tí ogun ò fi kó wọn. Bẹẹrẹ ní igbó àgàlà nílùú Ìbàdàn ni ó wà.
yor
Female
yor_1820
8
Ejo kan wo lo ninu gbo lojo kan nigba ti o se alabapade ile itaja ohun ija kan o fe mo ohun ajoji to wa ninu re ati awon eron nla n la to wa ninu re o wo lo si be nibi ti o tin wo kiri ninu ile itaja ohun ija na o seesi fara kan faili na ha lara inu bi ejo na o gbera n lo o si yipo o fe so sugbon nigba ti o la enure l...
yor
Male
yor_829
7
Méjìlá ní ọmọ adìye mi jẹ. Ṣugbọn ekejila won ti kú.
yor
Female
yor_1591
8
onigun meta alami iwe lori iyika olomi aro
yor
Male
yor_354
3
FCT Abuja ní olú ìlú Nàìjíríà.
yor
Female
yor_224
1
https://en.wikipedia.org/wiki/Geography Geography jẹ iwadi eleto ti Aaye (awọn ara ọrun miiran ti wa ni pato, gẹgẹbi "geography of Mars", tabi ti a fun ni orukọ miiran, gẹgẹbi areography ninu ọran Mars), awọn ẹya ara ẹrọ rẹ, ati awọn iyalenu ti o waye lori rẹ. 18][19][20] Fun ohunkan lati ṣubu sinu agbegbe ti ilẹ-aye, ...
yor
Female
yor_415
3
Àjọ NAFDAC so pé àwọn kò mọ̀ nípa ẹ̀sun tí ọ̀gá àgbà NPF fi kan àwọn ní orí ẹ̀rọ amóhùnmáwòràn Channels ní alẹ́ Ọjọ́bọ̀ tí ó kọjá.
yor
Female
yor_700
5
Ní alẹ́ ọjọ́ Àìkú, ọjọ́ Kọkànlá oṣù Kejì ọdún 2024 ni ìdíje ife ẹ̀yẹ ilẹ̀ Adúláwọ̀, African Cup of Nations (AFCON) wá sópin bí orílẹ̀ èdè Ivory Coast ṣe gbo ewúro sójú ikọ̀ agbábọ́ọ̀lù Nàìjíríà pẹ̀lú góòlù méjì sí ẹyọ̀kan. Super Eagles ló kọ́kọ́ ń léwájú nínú ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ náà nígbà tí balógun ikọ̀ agbábọ́ọ̀lù Nàìjíríà,...
yor
Female
yor_562
5
ìdáméta nínú mẹrin pèlú àmì ìsọdi púpò ọgọfà, àbájáde rẹ jẹ àádọrun
yor
Female
yor_1093
2
gbogbo ile Nigeria nje jollof rice ni osan Sunday
yor
Male
yor_39
1
ìwé mẹ́fà lori ara wọn
yor
Female
yor_1059
2
Anike ati abike gba ipo akọkọ ninu idanwo igbega ti o kẹhin
yor
Male
yor_1372
6
Osupa fun fun Loju Orun lale lori Omi
yor
Male
yor_1518
6
ECOWAS je Asoju fun Awon Orile Ede West African Gegebi bi EU se Je fun European Tiwon si Nba WHO, UNICEF, OPEC ati UNIDO se papo
yor
Male
yor_755
7
1. Tomato meji ati karọọti kàn. 2. Ere oko meji 3. Eso ẹlẹfọ meji wa papọ.
yor
Female
yor_914
7
Àjọ FIFA n palẹmọ ere idaraya ọlọdodún mẹrin mẹrin.
yor
Female
yor_54
1
Kí àwọn èèyàn máa múra sílẹ̀ de ojo alágbára lónìí
yor
Female
yor_1664
8
Odo nla po ni ile adulawo
yor
Male
yor_1051
2
moat ti ile-iṣẹ ohun-ini gidi ni awọn ile ati ilẹ fun tita julọ ni lekki ati Ajah ni Ipinle Eko (Lagos state)
yor
Male
yor_192
1
mo máa jo gidi gan lọjọ ikore to n bọ yii
yor
Female
yor_1640
8
merin lona marun je ogun
yor
Male
yor_100
1
Tọkùnrin tobìnrin tó bá ti bàlágà ló ní ̀ẹtọ́ láti f̣é ara wọn , kí ẉón sì dá ẹbí ti wọn sílẹ̀ láìsí ìkanilápá-kò kankan nípa ẹ̀ya wọn , tàbí orílè̀ẹ-èdè wọn tàbí ẹ̀sìn wọn. ̀Ẹtọ́ wọn dọ́gba nínú ìgbéyàwó, ìbáà jẹ́ nígbà tí ẉón wà pap̀ọ tàbí ḷéyìn tí won ba ko ara won A kò gbọ́dọ̀ ṣe ìgbeyàwó kan láìjẹ́ pé, àwọn tí ...
yor
Female
yor_448
3
Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́ Ẹ̀bùn Nobeli Orílẹ̀-èdè Sweden, Norway Bíbún láàkọ́kọ́ odun1901 Ibiìtakùn oníbiṣẹ́. Ẹ̀bùn Nobel (Ẹ̀bùn Nobel ní èdè Gẹ̀̀ẹ́̀si àti Nobelpriset ní ède Sweden Norwegian: Nobelprisen) ní àwọn èbùn odoódún káríayé tí àwọn ìgbìmọ̀ ará Scandinafia ń fún ni fún ìdámọ̀ ìmúlọsíwájú àṣà àti ìmọ̀...
yor
Female
yor_1586
8
Onigun meta meji pelu iyika laarin
yor
Male
yor_638
5
Dárúkọ ìkan lára àwọn òsere eré ìtàgé tí ó gbajúmọ̀ júlọ ni Nollywood? Funke Akindele wà lára àwọn òsere eré ìtàgé tí ó gbajúmọ̀ júlọ ni Nollywood
yor
Female
yor_947
7
Nariges Mohammadi jẹ ọmọ ìlú Irani ti a bi ni oṣù kẹrin, ọdun 1972. O jẹ akọwe iroyin ati ajafẹtọ-ọmọniyan nilu Irani. O gba ààmì ẹyẹ apọnle eniyan alaafia Lagbaye l'ọdun 2023 lẹyìn ti ìlú Irani ti wani iporuru lori iku arabinrin Jina Mahsa Amini ni ọdun 2022. Ni oṣù kẹwa, ọdun 2023, won Kede Mohammadi gẹgẹ bíi ẹni apọ...
yor
Female
yor_197
1
ọjọ ẹti ni gbogbo wa maa jade
yor
Female
yor_870
7
Ìlú wo lo pẹ koto gba ominira nilẹ adulawọ? Ilẹ Gúsù Adulawọ ni o pẹ koto gba ominira nilẹ adulawọ
yor
Female
yor_1342
4
Ó ṣòro gan-an fún Ìkookò láti dé ọ̀dọ̀ àgùntàn torí pé olùṣọ́ àgùntàn àtàwọn ajá rẹ̀ wà lójúfò. Ṣùgbọ́n lọ́jọ́ kan, ó rí awọ àgùntàn kan tí a bọ́ sí le si ẹ̀gbẹ́ kan, ó sì gbé e lé orí ìta rẹ̀, ó sì ń rìn lọ làárín àwọn àgùntàn. Ọdọ-Agutan ti o jẹ ti agutan, ti Ikooko wọ awo re,o bẹrẹ si tẹle Ikooko ni aṣọ Agutan. Ní d...
yor
Male
yor_691
5
Ǹjẹ́ iwò mọ ibi tí mọ fí ìgbànú yẹ́lò mi sí?
yor
Female
yor_455
3
David O. Oyedepo (ti a bi ni ọjọ́ kẹtà-dín-lọ́gbọ̀n oṣù kẹ̀sán ọdún 1954) jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, òjíṣẹ́ Ọlọ́run Biṣọọbu-àgbà, àti oludasile ìjọ Living Faith Church Worldwide (ìjọ ìgbàgbọ́ ààyè tó káríayé) ti gbogbo eniyan mo si Winners' Chapel (ìjọ aṣẹ́gun). [2] Olu-ijo yii fun gbogbo agbaye ni a tedo si ilu Ota ...
yor
Female
End of preview. Expand in Data Studio
README.md exists but content is empty.
Downloads last month
43