client_id
stringclasses 98
values | audio
audioduration (s) 2.16
10.5
| sentence
stringlengths 21
93
| up_votes
int64 2
16
| down_votes
int64 0
4
| age
stringclasses 4
values | gender
stringclasses 2
values | accents
stringclasses 4
values | variant
float64 | locale
stringclasses 1
value | segment
float64 |
|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|
8c2dccfe0f574150b34e7d1a1c6c70c0d012e0829150ec250d630cf66005beb06fce9ee64fdf0ed523e7d960a2311a3967267b94c064beb1522085fa9c17072f
|
Ó ti pé ọgọ́rùn-ún ọjọ́ tí ìjọba ti f'òfin de wá.
| 2
| 0
| null | null | null | null |
yo
| null |
|
00752441a5d1f86fc071c844e4e0d45873ff717b6fbc18b318b6ec8a5e121284210765d56238a3d1a5924c0b54c67b78197a2a57898518964e28d9ad32963b14
|
Gómìnà obìnrin ẹyọ kan péré la ti ní ní ìpínlẹ̀ Ayédé
| 2
| 0
| null | null | null | null |
yo
| null |
|
00752441a5d1f86fc071c844e4e0d45873ff717b6fbc18b318b6ec8a5e121284210765d56238a3d1a5924c0b54c67b78197a2a57898518964e28d9ad32963b14
|
Inú àbótí ńlá ni Àjàní kó gbogbo àwọn aṣọ rẹ̀ sí.
| 2
| 0
| null | null | null | null |
yo
| null |
|
2762548161d98f2bddd7b6191254fc0fa163c9d2c8283e9459b4cd00af8c2946d3ee7899fc647fa1cf2b137557de018298221b31a669b01d135efeb266537419
|
Kò sí ìwé ẹ̀rí fun olùdíje tí àwọn ẹgbẹ́ onígbàálẹ̀ fà kalẹ̀.
| 2
| 0
| null | null | null | null |
yo
| null |
|
2762548161d98f2bddd7b6191254fc0fa163c9d2c8283e9459b4cd00af8c2946d3ee7899fc647fa1cf2b137557de018298221b31a669b01d135efeb266537419
|
Àmọ̀tẹ́kùn ti gba àṣẹ ìdáábòbò lọ́wọ́ ìjọba.
| 2
| 0
| null | null | null | null |
yo
| null |
|
2f68e7bdcfd2cd0f90ad9a3f69a5ba0c2eb82982233212e7f445260e3e864411cd19ff5eff37adaa2f389b1cad7864e000d70ad14b11396080f4c3918be6d321
|
Ọ̀gá ni Bọ́lá jẹ́ fún Bọ̀dé lágbo òṣèlú.
| 2
| 0
| null | null | null | null |
yo
| null |
|
2f68e7bdcfd2cd0f90ad9a3f69a5ba0c2eb82982233212e7f445260e3e864411cd19ff5eff37adaa2f389b1cad7864e000d70ad14b11396080f4c3918be6d321
|
Àsìkò àjàkálẹ̀ ààrùn yìí jẹ́ kí n di télọ̀ tó mọṣẹ́ gidi.
| 2
| 0
| null | null | null | null |
yo
| null |
|
531bb085159fa258282593c65e8f689f71da07db82712a653ff818acdea426bf15107ea2bf02b695a8a35ad59c4fc3e51fc2c328a6cfe231527e648f4b7b606a
|
Ó ṣeé ṣe kí ọdún wáyé lábẹ́ àwọn òfin tuntun nípa arùn àjàkáyé
| 2
| 0
| null | null | null | null |
yo
| null |
|
531bb085159fa258282593c65e8f689f71da07db82712a653ff818acdea426bf15107ea2bf02b695a8a35ad59c4fc3e51fc2c328a6cfe231527e648f4b7b606a
|
Ọmọ àlè ti fi ilé jóná báyìí nílùú Ìbàdàn.
| 2
| 0
| null | null | null | null |
yo
| null |
|
f2480a3ceb786fc8c20c3fe5588f33d03f02f995f3422b6dd0d18e64b5b7ce32e0e184b962a08dcc2eb2611338428dcad0478d1ea4af2a19995e9d6d467cf92b
|
Àrẹ̀mú faraya lórí báwọn jàǹdùkú ṣe ń borí ọmọogun wa.
| 2
| 0
| null | null | null | null |
yo
| null |
|
f2480a3ceb786fc8c20c3fe5588f33d03f02f995f3422b6dd0d18e64b5b7ce32e0e184b962a08dcc2eb2611338428dcad0478d1ea4af2a19995e9d6d467cf92b
|
Ọ̀daràn mẹ́jọ ni wón mú ní ìlú Èrúwà lánàá.
| 2
| 0
| null | null | null | null |
yo
| null |
|
317e01cfa0a247f5b438af2cfc659c3a01975922ac379e229b59b38687573fd609a75a7b7c2fedeab092cf040a8527bd90f765516d16673df73e2db6c319d898
|
Lọ sí ilé Délé Gíwá láti wo àwọn akẹ́kọ̀ọ́ tó ń gbé ibẹ̀.
| 2
| 1
|
teens
|
female
| null | null |
yo
| null |
|
317e01cfa0a247f5b438af2cfc659c3a01975922ac379e229b59b38687573fd609a75a7b7c2fedeab092cf040a8527bd90f765516d16673df73e2db6c319d898
|
Àjọ elétò ìlera ti ní íjọba ti ra àwọn ohun ìgbógun ti ààrùn.
| 2
| 0
|
teens
|
female
| null | null |
yo
| null |
|
317e01cfa0a247f5b438af2cfc659c3a01975922ac379e229b59b38687573fd609a75a7b7c2fedeab092cf040a8527bd90f765516d16673df73e2db6c319d898
|
Omi gbé arákùnrin ẹni ọdún mẹ́tàlá kan lọ ní Ìbàdàn
| 2
| 0
|
teens
|
female
| null | null |
yo
| null |
|
3372937cd8fea4fdef33ac582dd80092bebff3a4ab7f7bd264c7df92891bf6c70ecfa43f5d7542d211f2c074b547c48558595f9a1ea47658a2732b990a11fa33
|
Àdúrà ò ní padà gbà mọ́ nígbà tí àbòsí bá ti pọ̀ jù.
| 3
| 0
| null | null | null | null |
yo
| null |
|
3372937cd8fea4fdef33ac582dd80092bebff3a4ab7f7bd264c7df92891bf6c70ecfa43f5d7542d211f2c074b547c48558595f9a1ea47658a2732b990a11fa33
|
Wo ohun tí òṣìṣẹ́ yìí ṣe tí ọ̀gá rẹ̀ fi fún ní ẹ̀bùn owó.
| 2
| 0
| null | null | null | null |
yo
| null |
|
3372937cd8fea4fdef33ac582dd80092bebff3a4ab7f7bd264c7df92891bf6c70ecfa43f5d7542d211f2c074b547c48558595f9a1ea47658a2732b990a11fa33
|
Agbẹjọ́rò ẹbí olóògbé Láwuyì ti yá owó ńlá kan ní báǹkì
| 2
| 0
| null | null | null | null |
yo
| null |
|
499127698e3af4fe79c2a895fa53f7670be98ab27b6a7874dd1b1b4784bbdf2904abf7ebdc979e2df1d7324a88790920601260d2320bba8d69df53c15d5bd5d6
|
Arákùnrin tí àwọn ọlọ́pàá mú ní òun kìí ṣe olè.
| 2
| 0
|
twenties
|
female
| null | null |
yo
| null |
|
499127698e3af4fe79c2a895fa53f7670be98ab27b6a7874dd1b1b4784bbdf2904abf7ebdc979e2df1d7324a88790920601260d2320bba8d69df53c15d5bd5d6
|
Àwọn Dókítà kan ti da iṣẹ́ sílẹ̀ nítorí àti gba owó lọ́wọ́ ìjọba
| 2
| 0
|
twenties
|
female
| null | null |
yo
| null |
|
499127698e3af4fe79c2a895fa53f7670be98ab27b6a7874dd1b1b4784bbdf2904abf7ebdc979e2df1d7324a88790920601260d2320bba8d69df53c15d5bd5d6
|
Tírélà agbépo ṣekúpa ọmọ ọdún méjì àti àwọn mẹ́ta míì
| 2
| 0
|
twenties
|
female
| null | null |
yo
| null |
|
a8b60a6491a33a5d8c602a9ed381061b507a86fca6f1f3ade890a20539baac40088dc24635035c7bf0f434bcfaca00fa0837ef69a84cae7020e7e2d141c100bc
|
Láàárín ìdílé ẹlẹ́ni márùn-ún yìí, ọmọ kan ṣoṣo ló léè sọ̀rọ̀.
| 2
| 0
|
twenties
|
female
| null | null |
yo
| null |
|
a8b60a6491a33a5d8c602a9ed381061b507a86fca6f1f3ade890a20539baac40088dc24635035c7bf0f434bcfaca00fa0837ef69a84cae7020e7e2d141c100bc
|
Òtútù àsìkò yìí pọ̀ lápọ̀ jù.
| 2
| 0
|
twenties
|
female
| null | null |
yo
| null |
|
a8b60a6491a33a5d8c602a9ed381061b507a86fca6f1f3ade890a20539baac40088dc24635035c7bf0f434bcfaca00fa0837ef69a84cae7020e7e2d141c100bc
|
Esì àyẹwò ọmọ ati ìyáwọ ọmọ Atiku ti jáde.
| 2
| 0
|
twenties
|
female
| null | null |
yo
| null |
|
e250e991b271786db85dbcaa00fd129ef4b041a9d988bd6dde7fdf54e4cd248f105740560e31d11643b8318fd1394a8847c4df867f07de276d9d668a6ea8607b
|
Àwọn Fúlàní ya bo ilé ìtura àwọn akẹ́kọ̀ọ́ wa
| 2
| 0
| null | null | null | null |
yo
| null |
|
e250e991b271786db85dbcaa00fd129ef4b041a9d988bd6dde7fdf54e4cd248f105740560e31d11643b8318fd1394a8847c4df867f07de276d9d668a6ea8607b
|
Wọ́n fi Ṣàǹgó búra fún ààrẹ Nàìjíríà tuntun.
| 2
| 0
| null | null | null | null |
yo
| null |
|
e250e991b271786db85dbcaa00fd129ef4b041a9d988bd6dde7fdf54e4cd248f105740560e31d11643b8318fd1394a8847c4df867f07de276d9d668a6ea8607b
|
Wọ́n ti rán Adéṣọlá lọ ésí ẹ̀wọ̀n ọdún méjìlélọ́gbọ̀n
| 2
| 0
| null | null | null | null |
yo
| null |
|
e613f3107bc572d99cd2d09ade387ab57132cd5f6bc13508e059781bab289e7a2c2a41a0c14fdfd3741e58aba45c00d7a98162bc36638d13a1383131cc648b49
|
Ìyálé mi ti di ẹ̀rùjẹ̀jẹ̀ nínú ìlú, kò sí ẹni tó le múu
| 2
| 0
| null | null | null | null |
yo
| null |
|
e613f3107bc572d99cd2d09ade387ab57132cd5f6bc13508e059781bab289e7a2c2a41a0c14fdfd3741e58aba45c00d7a98162bc36638d13a1383131cc648b49
|
Ọkọ àti ìyàwó ti gbọ̀nà oko lọ láti àárọ̀.
| 2
| 0
| null | null | null | null |
yo
| null |
|
e613f3107bc572d99cd2d09ade387ab57132cd5f6bc13508e059781bab289e7a2c2a41a0c14fdfd3741e58aba45c00d7a98162bc36638d13a1383131cc648b49
|
Ilé ẹjọ́ gíga wọ́gilé ìyọnípò Àdìsá gẹ́gẹ́ bíi alága ẹgbẹ́ rẹ̀.
| 2
| 0
| null | null | null | null |
yo
| null |
|
f145cc066e9ca0aa98a668f0d80a04ea8e75b75259548eef791f74d2d15db8f6caf6ceef2b20bad7231f604bd1e31cc3fee6466c84e9560a8846bc9e656c0e07
|
Ẹnìkan pe àwọn wí pé ilé kan ń jó ní agbègbè náà.
| 2
| 0
| null | null |
Ohùn ìpèdè mi ni Yorùbá àwùjọ
| null |
yo
| null |
|
f145cc066e9ca0aa98a668f0d80a04ea8e75b75259548eef791f74d2d15db8f6caf6ceef2b20bad7231f604bd1e31cc3fee6466c84e9560a8846bc9e656c0e07
|
Ọwá Obòkun ni orúkọ ọba ìlú Iléshà, Ajerò ni ti Ìjerò
| 2
| 0
| null | null |
Ohùn ìpèdè mi ni Yorùbá àwùjọ
| null |
yo
| null |
|
f145cc066e9ca0aa98a668f0d80a04ea8e75b75259548eef791f74d2d15db8f6caf6ceef2b20bad7231f604bd1e31cc3fee6466c84e9560a8846bc9e656c0e07
|
Túndé kó sí gbaga ọlọ́pàá nítórí ikú ọmọ ọdún mẹ́wàá kan.
| 2
| 0
| null | null |
Ohùn ìpèdè mi ni Yorùbá àwùjọ
| null |
yo
| null |
|
f2ed009526a9dae3576763cf76adcbdd52fc527a00564954df8bd1ebafd2d500070fc0febe907b5fa4ccfff5f7c8eff9a9cde1152546a821f27f71877e849b65
|
Ó tẹ̀síwájú pé kò sí ẹnikẹ́ni tó farapa níbi ìṣẹ̀lẹ̀ náà.
| 2
| 0
| null | null | null | null |
yo
| null |
|
f2ed009526a9dae3576763cf76adcbdd52fc527a00564954df8bd1ebafd2d500070fc0febe907b5fa4ccfff5f7c8eff9a9cde1152546a821f27f71877e849b65
|
Lékan ní òun kò lérò pé òun le mókè nínú iṣẹ́ orin.
| 2
| 1
| null | null | null | null |
yo
| null |
|
f2ed009526a9dae3576763cf76adcbdd52fc527a00564954df8bd1ebafd2d500070fc0febe907b5fa4ccfff5f7c8eff9a9cde1152546a821f27f71877e849b65
|
Pásítọ̀ na àwọn ọmọ ìjọ láti mọ̀ bí wọn ṣe gbóná fún Ọ́lọ́run tó.
| 2
| 0
| null | null | null | null |
yo
| null |
|
2967cb4b90314efbe4035ab0e08c3dbc566b49603838f481928ec924abdbba9a69db890b0cc5a4ccef66d6a0ed528518781058172d23264d276cf0e87a258b07
|
Gómìnà Makinde bá mọ̀lẹ́bí ọkùnrin náà kẹ́dùn lọ́jọ́ náà
| 2
| 1
| null | null | null | null |
yo
| null |
|
2967cb4b90314efbe4035ab0e08c3dbc566b49603838f481928ec924abdbba9a69db890b0cc5a4ccef66d6a0ed528518781058172d23264d276cf0e87a258b07
|
Ìjọba àpapọ̀ ń sọ̀rọ̀ tòótọ́ fún wa.
| 2
| 0
| null | null | null | null |
yo
| null |
|
2967cb4b90314efbe4035ab0e08c3dbc566b49603838f481928ec924abdbba9a69db890b0cc5a4ccef66d6a0ed528518781058172d23264d276cf0e87a258b07
|
Ìwòsàn ló bá Kẹ́mi dáwọ́ ìtọ̀ dúró.
| 2
| 0
| null | null | null | null |
yo
| null |
|
2967cb4b90314efbe4035ab0e08c3dbc566b49603838f481928ec924abdbba9a69db890b0cc5a4ccef66d6a0ed528518781058172d23264d276cf0e87a258b07
|
Túńdé pe gbogbo ẹgbẹ́ jọ láti sọ fún wọn pé kí wọ́n gbaradì.
| 2
| 0
| null | null | null | null |
yo
| null |
|
31edf400b70d6669ca0e3bdd3b7a9b240e98c2be577a48e00cd396d3aa549c0ad2db3560852e2dbd95fc1339c726835ee9afe393f45c78c03ca80f48392745a7
|
Bí àwọn ará ìlú ṣe fara mọ́ ṣíse àbẹ́rẹ́ àjẹsára ni mo ta kò
| 2
| 0
|
twenties
|
female
| null | null |
yo
| null |
|
31edf400b70d6669ca0e3bdd3b7a9b240e98c2be577a48e00cd396d3aa549c0ad2db3560852e2dbd95fc1339c726835ee9afe393f45c78c03ca80f48392745a7
|
Ẹ̀bà gígan ni Bísí jẹ sùn lánàá.
| 2
| 1
|
twenties
|
female
| null | null |
yo
| null |
|
31edf400b70d6669ca0e3bdd3b7a9b240e98c2be577a48e00cd396d3aa549c0ad2db3560852e2dbd95fc1339c726835ee9afe393f45c78c03ca80f48392745a7
|
Awọn akọ́mọlédè lórílẹ̀ èdè yìí ti rọ àwọn ọmọ Yorùbá lóyè
| 2
| 0
|
twenties
|
female
| null | null |
yo
| null |
|
31edf400b70d6669ca0e3bdd3b7a9b240e98c2be577a48e00cd396d3aa549c0ad2db3560852e2dbd95fc1339c726835ee9afe393f45c78c03ca80f48392745a7
|
Ẹgbẹ́ fún ìdàgbàsókè ọrọ̀ ajé ti fún àwọn obìnrin lówó níbàdàn.
| 2
| 0
|
twenties
|
female
| null | null |
yo
| null |
|
3958571ee09f0b903048a5cb743b1a51726ab41ea53f819ddb2ce67c813a6179471d5fb218d9ef5c8a641a509c91c2ea373f019d9b8362208edd5b10f9289f67
|
Nínú Ọlọ́pàá àti ààrùn jẹjẹrẹ, èwo ló yẹ ka bẹ̀rù?
| 2
| 0
| null | null | null | null |
yo
| null |
|
3958571ee09f0b903048a5cb743b1a51726ab41ea53f819ddb2ce67c813a6179471d5fb218d9ef5c8a641a509c91c2ea373f019d9b8362208edd5b10f9289f67
|
Àwọn àgbàgbà ọlọ́pàá ti ṣàánú ọmọbìnrin tí wọn gbámú
| 2
| 0
| null | null | null | null |
yo
| null |
|
3958571ee09f0b903048a5cb743b1a51726ab41ea53f819ddb2ce67c813a6179471d5fb218d9ef5c8a641a509c91c2ea373f019d9b8362208edd5b10f9289f67
|
Àwọn aṣòfin ilẹ̀ Nàìjíríà ṣọ̀rọ̀ ìwúrí nípa Ajímọ̀bí.
| 2
| 0
| null | null | null | null |
yo
| null |
|
3958571ee09f0b903048a5cb743b1a51726ab41ea53f819ddb2ce67c813a6179471d5fb218d9ef5c8a641a509c91c2ea373f019d9b8362208edd5b10f9289f67
|
Olórí gbọ́dọ̀ jẹ́ ẹni tó lóòótọ́, tí ò ní máa ṣọ̀tún-ṣòsì.
| 2
| 0
| null | null | null | null |
yo
| null |
|
4e074e2e437647508dd8800e32bb6d313ce841e6b24cfcdcd8136b78b4705a950716c60b5146531a89c3a3c4995907da2d7497e5f2389ad2b064a027b137b10f
|
Olúọmọ oṣòdì má gbé jàgídíjàgan wá.
| 2
| 1
| null | null | null | null |
yo
| null |
|
4e074e2e437647508dd8800e32bb6d313ce841e6b24cfcdcd8136b78b4705a950716c60b5146531a89c3a3c4995907da2d7497e5f2389ad2b064a027b137b10f
|
Ẹ tẹ ọkùnrin tó bá fipá bá obìnrin lòpọ̀ ní ọ̀dá, ìwà ìkà ni.
| 2
| 1
| null | null | null | null |
yo
| null |
|
4e074e2e437647508dd8800e32bb6d313ce841e6b24cfcdcd8136b78b4705a950716c60b5146531a89c3a3c4995907da2d7497e5f2389ad2b064a027b137b10f
|
Ìdí tí Ìyábọ̀ Ọbásanjọ́ fi ṣe pàtàkì ní ìpínlẹ̀ Ògùn nìyí o
| 2
| 1
| null | null | null | null |
yo
| null |
|
4e074e2e437647508dd8800e32bb6d313ce841e6b24cfcdcd8136b78b4705a950716c60b5146531a89c3a3c4995907da2d7497e5f2389ad2b064a027b137b10f
|
Àjẹ́ ni àwọn ìyá Àjànàkú àti Àlàbí.
| 3
| 0
| null | null | null | null |
yo
| null |
|
717ddb0a5510869663c951605ea56a1ca62753e433f7b009e579ce09bb9e6851dae2aa7c49620dc7167bfb7b9dafca5168d6cb10006cc54be8eb6f7287872bf3
|
Mo fẹ́ bá àwọn ọmọ Ajílẹ́yẹ ṣeré fún bí ọdún mẹ́ta síi
| 2
| 0
| null | null | null | null |
yo
| null |
|
717ddb0a5510869663c951605ea56a1ca62753e433f7b009e579ce09bb9e6851dae2aa7c49620dc7167bfb7b9dafca5168d6cb10006cc54be8eb6f7287872bf3
|
Ikú burúkú ló pa ìyàwó Rẹ̀mí ní ìjẹrin.
| 2
| 0
| null | null | null | null |
yo
| null |
|
717ddb0a5510869663c951605ea56a1ca62753e433f7b009e579ce09bb9e6851dae2aa7c49620dc7167bfb7b9dafca5168d6cb10006cc54be8eb6f7287872bf3
|
Ẹni tí ò bá lérò, tí ò létò, o lè jẹ́ olórí ti wa.
| 2
| 0
| null | null | null | null |
yo
| null |
|
717ddb0a5510869663c951605ea56a1ca62753e433f7b009e579ce09bb9e6851dae2aa7c49620dc7167bfb7b9dafca5168d6cb10006cc54be8eb6f7287872bf3
|
Olúmidé ti rọ àwọn ènìyàn pé kí wọn má fojú òṣèlú wo àbẹ̀wò òun.
| 2
| 0
| null | null | null | null |
yo
| null |
|
73e2274d3da430369e7960696ce03c9e9d03b92f1c2a6c1969f3b67d3548f55b4c3cc7726bfec9069af0f2155d784547242801aefe826d0229e07a4ffe98edd5
|
Ǹkan mẹ́ta ló fàá tí jàndùkú fi ń yìnbọn pa àwọn ọlọ́pàá
| 2
| 0
| null | null | null | null |
yo
| null |
|
73e2274d3da430369e7960696ce03c9e9d03b92f1c2a6c1969f3b67d3548f55b4c3cc7726bfec9069af0f2155d784547242801aefe826d0229e07a4ffe98edd5
|
Àwọn aṣewádìí náà gbọ́dọ̀ ri pé wọ́n ṣe ìwádìí wọn fínnífínní
| 2
| 0
| null | null | null | null |
yo
| null |
|
73e2274d3da430369e7960696ce03c9e9d03b92f1c2a6c1969f3b67d3548f55b4c3cc7726bfec9069af0f2155d784547242801aefe826d0229e07a4ffe98edd5
|
Wọ́n ní àwọn méjìlá ní wọ́n bódòlọ.
| 2
| 0
| null | null | null | null |
yo
| null |
|
73e2274d3da430369e7960696ce03c9e9d03b92f1c2a6c1969f3b67d3548f55b4c3cc7726bfec9069af0f2155d784547242801aefe826d0229e07a4ffe98edd5
|
Adébimpé gba omijé lójú Adédiméjì.
| 2
| 1
| null | null | null | null |
yo
| null |
|
9c76fa3e7c99e5e0fb385acfb938663871bc435a88015abc268cfb844f6bb88a3bde96967c92579421e048b45723929300a37b25a578568dd0f2ef4e874d778a
|
Àwọn jàndùkú jí Rẹ̀mí gbé.
| 2
| 0
| null | null | null | null |
yo
| null |
|
9c76fa3e7c99e5e0fb385acfb938663871bc435a88015abc268cfb844f6bb88a3bde96967c92579421e048b45723929300a37b25a578568dd0f2ef4e874d778a
|
Ọwọ́ ọlọ́pàá tẹ arákùrin ajínigbé kan ní ìlú Òṣogbo.
| 2
| 1
| null | null | null | null |
yo
| null |
|
9c76fa3e7c99e5e0fb385acfb938663871bc435a88015abc268cfb844f6bb88a3bde96967c92579421e048b45723929300a37b25a578568dd0f2ef4e874d778a
|
Bùhárí ń bèèrè fún àforíjìn gbèsè tí a jẹ lọ́dọ̀ àjọ àgbáyé
| 2
| 1
| null | null | null | null |
yo
| null |
|
9c76fa3e7c99e5e0fb385acfb938663871bc435a88015abc268cfb844f6bb88a3bde96967c92579421e048b45723929300a37b25a578568dd0f2ef4e874d778a
|
Ìpinu mi fọ́dún yìí ni láti yí padà si obìnrin pátápátá.
| 2
| 0
| null | null | null | null |
yo
| null |
|
a204d97ec2ca679663388e53feaceba53fb6500b8c047795cc91723615fd6a38b93fcbac6435e0a152cdf2f71a4f96232a45c89a875e6473157ecd93ef074744
|
Àwa la gbé ìgbá orókè nínú ìdíje eré bọ́ọ̀lù ní Ìbàdàn
| 2
| 1
| null | null | null | null |
yo
| null |
|
a204d97ec2ca679663388e53feaceba53fb6500b8c047795cc91723615fd6a38b93fcbac6435e0a152cdf2f71a4f96232a45c89a875e6473157ecd93ef074744
|
Bílíònú mẹ́fà ni ìjọba ìpínlẹ̀ Ekiti yòó ná lórí Àmọ̀tẹ́kùn.
| 2
| 0
| null | null | null | null |
yo
| null |
|
a204d97ec2ca679663388e53feaceba53fb6500b8c047795cc91723615fd6a38b93fcbac6435e0a152cdf2f71a4f96232a45c89a875e6473157ecd93ef074744
|
Gómìnà Ọbásànyà yọ ọ̀gá ikọ̀ ọlọ́pàá nípò.
| 2
| 0
| null | null | null | null |
yo
| null |
|
a204d97ec2ca679663388e53feaceba53fb6500b8c047795cc91723615fd6a38b93fcbac6435e0a152cdf2f71a4f96232a45c89a875e6473157ecd93ef074744
|
Adéwálé fèsì padà pé àwọn àgbààgbà tó ní owó lọ́wọ́ wà níbẹ̀.
| 2
| 1
| null | null | null | null |
yo
| null |
|
a2968a522815c9d2b62a33cf86c779447d3c49edd1697cb7752ef6b23e7f0d8d83b3857e0a51a6987bb7d5f649f5bf38e6309e90d1e129f79183cc47d3b06fd7
|
Ṣé lóòtọ́ ni pé ilé ẹjọ́ sọ pé kí Àrẹ̀mú lọ sí ẹ̀wọ̀n.
| 2
| 0
| null | null | null | null |
yo
| null |
|
a2968a522815c9d2b62a33cf86c779447d3c49edd1697cb7752ef6b23e7f0d8d83b3857e0a51a6987bb7d5f649f5bf38e6309e90d1e129f79183cc47d3b06fd7
|
Wo ọ̀nà láti jẹ ànfàní ìforúkọsílẹ ọ̀fẹ́ tí ìjọba gbékalẹ̀.
| 2
| 0
| null | null | null | null |
yo
| null |
|
a2968a522815c9d2b62a33cf86c779447d3c49edd1697cb7752ef6b23e7f0d8d83b3857e0a51a6987bb7d5f649f5bf38e6309e90d1e129f79183cc47d3b06fd7
|
Sanwó Olú ti gba àwòrán apanilẹ́rín kan nílùú Èkó.
| 2
| 0
| null | null | null | null |
yo
| null |
|
a2968a522815c9d2b62a33cf86c779447d3c49edd1697cb7752ef6b23e7f0d8d83b3857e0a51a6987bb7d5f649f5bf38e6309e90d1e129f79183cc47d3b06fd7
|
Ọwọ́ àwọn agbófinró tẹ afurasú oníjìbìtì tó lu Kẹ́mi ní jìbìtì owó.
| 2
| 0
| null | null | null | null |
yo
| null |
|
be9f8d752adf580125074847d6190276cab4293e3400446a3d1f5922e3ddaa7e53d94104b66fa766f726d211e06be08d6ec118a67675be1080b63bdc9a417b90
|
Wo ìkílọ̀ Ìjọba àpapọ̀, Ọlọ̀pàá àti Gómìnà Sanwó-olú.
| 2
| 0
| null | null | null | null |
yo
| null |
|
be9f8d752adf580125074847d6190276cab4293e3400446a3d1f5922e3ddaa7e53d94104b66fa766f726d211e06be08d6ec118a67675be1080b63bdc9a417b90
|
Ààrẹ àkọ́kọ́ ní Ọ̀yọ́ jáde láyé.
| 2
| 0
| null | null | null | null |
yo
| null |
|
be9f8d752adf580125074847d6190276cab4293e3400446a3d1f5922e3ddaa7e53d94104b66fa766f726d211e06be08d6ec118a67675be1080b63bdc9a417b90
|
Mo ní kí wọ́n yé ṣe àwáwí fún bàbá Ìjẹ̀shà fún oun tó ṣẹ
| 2
| 0
| null | null | null | null |
yo
| null |
|
be9f8d752adf580125074847d6190276cab4293e3400446a3d1f5922e3ddaa7e53d94104b66fa766f726d211e06be08d6ec118a67675be1080b63bdc9a417b90
|
Àwọn èèyàn pàdánù ẹ̀mí wọn nínú ìjàmbá ọkọ ní Èkó.
| 2
| 1
| null | null | null | null |
yo
| null |
|
c5ab7046df2c628550dcc797e52075670db5f2df16242ed18e82ae4b4f676077a9981091356d3121e1b574ed15012cccb5f8de454c62c5373c2691310823bf19
|
Orilẹ ede Nàìjíríà ni lati ni ilọsiwaju ninu iṣẹ sinimá.
| 2
| 0
| null | null | null | null |
yo
| null |
|
c5ab7046df2c628550dcc797e52075670db5f2df16242ed18e82ae4b4f676077a9981091356d3121e1b574ed15012cccb5f8de454c62c5373c2691310823bf19
|
Ẹni tó fí ìbínú lu Ábúdù ọlọ́kadà pa ní Abẹ́òkuta ti sálọ.
| 2
| 0
| null | null | null | null |
yo
| null |
|
c5ab7046df2c628550dcc797e52075670db5f2df16242ed18e82ae4b4f676077a9981091356d3121e1b574ed15012cccb5f8de454c62c5373c2691310823bf19
|
Ayẹyẹ elégún yẹn yóò párí ní Ọjọ́ Ajé tó ń bọ̀.
| 2
| 0
| null | null | null | null |
yo
| null |
|
c5ab7046df2c628550dcc797e52075670db5f2df16242ed18e82ae4b4f676077a9981091356d3121e1b574ed15012cccb5f8de454c62c5373c2691310823bf19
|
Odùduwà sọ fún Oyètọ́lá nípa ọ̀gá ilé ìwé mẹ́ta tó dá dúró
| 2
| 0
| null | null | null | null |
yo
| null |
|
ed17df6a60b7d4c551242913b2aef4b3de95ba58d48d105d4b3b489760bddf4dbf549772369f6954ba99548724957de5e61de358e0c3fcd9597967c6ff6123ef
|
Ojú ẹni máa là, á rí tó lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà.
| 2
| 0
| null | null | null | null |
yo
| null |
|
ed17df6a60b7d4c551242913b2aef4b3de95ba58d48d105d4b3b489760bddf4dbf549772369f6954ba99548724957de5e61de358e0c3fcd9597967c6ff6123ef
|
Wọ́n ti kéde ètò ìsìnkú Ajímájàṣán àti ọjọ́ tí wọn yóò sin-ín
| 2
| 0
| null | null | null | null |
yo
| null |
|
ed17df6a60b7d4c551242913b2aef4b3de95ba58d48d105d4b3b489760bddf4dbf549772369f6954ba99548724957de5e61de358e0c3fcd9597967c6ff6123ef
|
Adébáyò wá kábàámọ̀ pé ọ̀pọ̀ nǹkan ni wọ́n ń tọwọ́ òṣèlú bọ.
| 2
| 0
| null | null | null | null |
yo
| null |
|
ed17df6a60b7d4c551242913b2aef4b3de95ba58d48d105d4b3b489760bddf4dbf549772369f6954ba99548724957de5e61de358e0c3fcd9597967c6ff6123ef
|
Ọdún kẹ́ta rẹ̀é ti ọkọ àti ìyàwó ò tí ì bímọ.
| 2
| 0
| null | null | null | null |
yo
| null |
|
fc34f70621f47ebb8f316e1263238eedd97a7aff4b8edfd99d220c762502d5b767b63ae3727a970e49ed7fd7d6c833d0ab7db9f392dac787e734a7a4c8e18c22
|
Ìbànújẹ́ gba ìlú kan nígbà tí àṣìta ìbọn ba ọmọ ọdún méjì kan.
| 2
| 0
| null | null | null | null |
yo
| null |
|
fc34f70621f47ebb8f316e1263238eedd97a7aff4b8edfd99d220c762502d5b767b63ae3727a970e49ed7fd7d6c833d0ab7db9f392dac787e734a7a4c8e18c22
|
Lọ́dọ̀ àwọn agbẹjọ́rò tó ń gbé Ìshẹri ni mo ti kọ́kọ́ gbọ́ ẹjọ́ rẹ̀
| 2
| 0
| null | null | null | null |
yo
| null |
|
fc34f70621f47ebb8f316e1263238eedd97a7aff4b8edfd99d220c762502d5b767b63ae3727a970e49ed7fd7d6c833d0ab7db9f392dac787e734a7a4c8e18c22
|
Màmá tó jẹ́ onímọ̀ òye kọjá lọ ní àárọ̀ kùtùkùtù lánàá
| 2
| 0
| null | null | null | null |
yo
| null |
|
fc34f70621f47ebb8f316e1263238eedd97a7aff4b8edfd99d220c762502d5b767b63ae3727a970e49ed7fd7d6c833d0ab7db9f392dac787e734a7a4c8e18c22
|
Wọ́n ní kí àwọn èèyàn dẹ́kun láti máa pe àwọn obìnrin ní aṣéwó.
| 2
| 0
| null | null | null | null |
yo
| null |
|
0d12aa8b6854acc1e9f93e813e693ff795624580d7d05ffdcee8d521fea4ca1985b23cfde939130afe12cd96fbf6045718fe816bb38afd5b5b2d57faef16cb70
|
Àwọn ológun ti gbàjọba ní ìlú kan tó wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ Odò Ọya
| 2
| 0
| null | null | null | null |
yo
| null |
|
0d12aa8b6854acc1e9f93e813e693ff795624580d7d05ffdcee8d521fea4ca1985b23cfde939130afe12cd96fbf6045718fe816bb38afd5b5b2d57faef16cb70
|
Gómìnà Oyètọ́lá ti pè fún alàáfíà láàrin àwọn ọmọ ẹgbẹ́ rẹ̀
| 2
| 0
| null | null | null | null |
yo
| null |
|
0d12aa8b6854acc1e9f93e813e693ff795624580d7d05ffdcee8d521fea4ca1985b23cfde939130afe12cd96fbf6045718fe816bb38afd5b5b2d57faef16cb70
|
Amọ̀fin tó ń ṣáájú ikọ̀ agbẹjọ́rò fún ẹgbẹ́ náà ní ìlànà.
| 2
| 0
| null | null | null | null |
yo
| null |
|
0d12aa8b6854acc1e9f93e813e693ff795624580d7d05ffdcee8d521fea4ca1985b23cfde939130afe12cd96fbf6045718fe816bb38afd5b5b2d57faef16cb70
|
Iléẹjọ́ ṣe ìdájọ́ iléìfowópamọ́ lori ìwà jìbìtì.
| 2
| 0
| null | null | null | null |
yo
| null |
|
0d12aa8b6854acc1e9f93e813e693ff795624580d7d05ffdcee8d521fea4ca1985b23cfde939130afe12cd96fbf6045718fe816bb38afd5b5b2d57faef16cb70
|
Ọlá yóò gúnlẹ̀ sí Ọ̀yọ́ ní ọ̀sẹ̀ tó ń bọ̀.
| 2
| 0
| null | null | null | null |
yo
| null |
|
3243b38db01f713f29a8e0b2fee0c3f99c334ee64b4fcf255b8740a7d9b7e78799bdbc88ba52f04162ddad0937e4d4cec21ba11cb8c7afc899697c91ed9b8a04
|
Èmi àti Túndé ti kọ́ ẹ̀kọ́ síi nípa ààlọ́ Yorùbá
| 2
| 0
| null | null | null | null |
yo
| null |
|
3243b38db01f713f29a8e0b2fee0c3f99c334ee64b4fcf255b8740a7d9b7e78799bdbc88ba52f04162ddad0937e4d4cec21ba11cb8c7afc899697c91ed9b8a04
|
Kí lẹ̀ ń bú ààrẹ fún nítorí Ọlọ́run.
| 2
| 0
| null | null | null | null |
yo
| null |
|
3243b38db01f713f29a8e0b2fee0c3f99c334ee64b4fcf255b8740a7d9b7e78799bdbc88ba52f04162ddad0937e4d4cec21ba11cb8c7afc899697c91ed9b8a04
|
Ènìyàn mẹjọ mìíràn tún ti ní ààrùn jẹjẹrẹ ní Nàìjíríà.
| 2
| 0
| null | null | null | null |
yo
| null |
|
3243b38db01f713f29a8e0b2fee0c3f99c334ee64b4fcf255b8740a7d9b7e78799bdbc88ba52f04162ddad0937e4d4cec21ba11cb8c7afc899697c91ed9b8a04
|
Ọkùnrin nìkan náà ni ó lè wo orò ní ilẹ̀ Yorùbá.
| 2
| 0
| null | null | null | null |
yo
| null |
|
3243b38db01f713f29a8e0b2fee0c3f99c334ee64b4fcf255b8740a7d9b7e78799bdbc88ba52f04162ddad0937e4d4cec21ba11cb8c7afc899697c91ed9b8a04
|
Rẹ̀mi ti kú nípa ìkọlù tó wáyé.
| 2
| 1
| null | null | null | null |
yo
| null |
|
38cc26a1a3d7c12de743b1457eacfee7c857e757cec0f3ab740dc8183e97e2e8eb5892049b3e54503750660d4230bee65dc6845f204f10dae5f202ff44187fbb
|
Àwọn olórí Yorùbá ti ní kò ní sí ètò ìdìbò lọ́dún tó ń bọ̀.
| 2
| 0
| null | null | null | null |
yo
| null |
|
38cc26a1a3d7c12de743b1457eacfee7c857e757cec0f3ab740dc8183e97e2e8eb5892049b3e54503750660d4230bee65dc6845f204f10dae5f202ff44187fbb
|
Ìtàn málegbàgbé ni àwọn ìtàn akọni bíi Mọ́remí ní àwùjọ Yorùbá.
| 2
| 0
| null | null | null | null |
yo
| null |
|
38cc26a1a3d7c12de743b1457eacfee7c857e757cec0f3ab740dc8183e97e2e8eb5892049b3e54503750660d4230bee65dc6845f204f10dae5f202ff44187fbb
|
Adébóyè ní ọ̀pọ̀ nǹkan ńlá ni yóò ṣẹlẹ̀ lẹ́yìn ìgbélé ààrùn.
| 2
| 0
| null | null | null | null |
yo
| null |
End of preview. Expand
in Data Studio
This dataset contains the validated part of IroyinSpeech.
Hours of data : 5
- Downloads last month
- 24