Dataset Viewer
Auto-converted to Parquet Duplicate
line_id
stringlengths
4
4
audio
audioduration (s)
7.56
906
text
stringlengths
49
2.88k
speaker_id
stringlengths
2
2
01yy
a àga b bàtà d dùndún e ehoro е eşin f filà g garawa gb gbágùúdá h hanrun i igi j jígí k kókóró | légbélégbé m mángòrò n náírà o ológbò ọ òbọ p pépéye r ràkúnmí s sálúbàtà t u W y tata tú wárápá yanmùyánmú
01
02yy
b bàtà d dùndú f filà g igi gb gbogbo k kó̟kó̟ró l labalábá m méjì n nísisìnyí p pátápátá r rìkísí s sálúbàtà ş şibĺ t tata w wàrà y yanmùyánmú
02
03yy
an en in ọn un 'Ìbàdàn' 'iyen' 'erin' 'ìbon' 'fun'
03
04yy
a ajá e erin е -- i O u บ eye imú owó o̟wó̟ *ooru
04
06yy
Ę kááárò o, bàbá. Kááárò o, Tádé. Şé o sùn dáadáa? Béè ni, mo sùn dáadáa. Ę ṣé. Ę káàbò o, Màmá Kúulé O, Lolá. Şé àlàáfíà ni? Alàáfíà ni. Egbónon rẹ ńkó̟? Won wà nílé. Ó dáa o. Dìde. Ẹ káàárò mà. Ę kááárò o. Sé dáadáa ni o? Dáadáa ni mà. Şé e sùn dáadáa? Bé̟è̟ ni mà. Káásán o, Fúnmi. Káásán o, Şadé. Şé dáadáa ni? A ...
06
07yy
Orúkọo mi ni Wálé. Mo jé̟ akékò̟ó ní Yunifásítì ti Texas ní Austin. Mo férán ilé-ìwéè mi gan-an ni nítorí pé gbogbo ohun tí ó lè mú kí è̟kó̟ rọ ènìyàn lórùn ni ó wà níbè àgàgà nínú kíláȧsìì mi. Orişirişi nǹkan ni ó wà nínú kíláàsìì mi. Láraa wọn ni àga, tábìlì, àwòrán, kò̟ǹpútà, monito, máòsì, kíĺboodù, ìwé atúmò̟-èdè,...
07
08yy
Gbogbo yín, e mú ìwé ìṣiròo yín jáde. Ę şí ìwé yín sí ojú-ìwé karùnlélógbon. Títí, s̟e ìṣirò kìíní. Aárùnúndínlógún àti eétàlá jé eéjìdínló̟gbon. Títí, o gba ìşirò rẹ şámúṣámú. Kémi, şe ìşirò kọkànlá. Yọ ẹérin kúrò nínú eétàlá. Em em em, ó ku ẹésànán. O káre, Kémi. Foláké, s̟e ìşirò tó télé ìyẹn. Yọ ẹésànán kúrò nínú e...
08
09yy
Bàbá Olá, şé wà á bámi lọ sí oko ní ò̟sè̟ tí ó ń bò̟? Rárá o, nítorí pé mo máa lọ sí ò̟dò̟ àbúròò mi obìnrin tí ara rè̟ kò yá. Tí mo bá dé ibè, mà á ba lọ sí oko láti mú ișu, ilá, tòmátò, è̟gúsí, ata rodo, tàtàsé àti ègé wá sílé. Tí mo bá dé láti oko, mà á ba se oúnjẹ. Léyìn náà, mà á ní láti bá a foṣọ, lọta, kí n sì b...
09
10yy
Orúkọ mi ni Wálé. Mo jé̟ o̟mo̟ bíbí ìlú Ìbàdàn láti ìpínlè̟ Òyó̟ ní orílè̟-èdè Nàìjíríà. Tí ó bá di ojó kesàn-án, oṣù kọkànlá ọdún tí ó ń bò̟ ni màá pé ọmọ ọdún mókándínlógbon. Gégé bí ìtàn tí mo gbó̟, torí bí ọmọdé kò bá gbó̟ ìtàn, yóò gbó̟ àró̟bá torí pé àróbá ni bàbá ìtàn. Mo gbó pé ojó ìṣégun ni ojó tí àwọn òbíì mi...
10
11yy
Fèyí, ṣé wà á wá kí mi ní òpin osè, ní ojó àìkú? Ní aago mélòó ni o fé kí n wá? ó máa dára ní ò̟sán nítorí pé mo máa ń lọ sí ìsìn o̟mo̟dé ní aago mésànán àbò àárò. Léyìn náà, ní aago mewa, ìsìn àgbà máa bèrè. (Èmi náà), ní aago márùnún ìrolé, mo ń lo sí ibi ojo ìbí ò̟réè mi kan. Ojo ìbli ta ni? Ojó ìbí Akin Ọmóyemí. Rá...
11
12yy
Yemí, Ọmọ ọdún mélòó ni é? Ọmọ ọdún méjìdínlógún ni mí. Ọmọ ọdún mélòó ni bàbáà rę? Ọmọ ọdún métalélógójì ni wó̟n. Ọmọ ọdún mélòó ni mȧmáà rę? Ọmọ ogójì odún ni won. Ọmọ ọdún mélòó ni àbúròo bàbáà rę? Ọmọ ogbon odún ni won. Ọmọ ọdún mélòó ni è̟gbó̟nòn rẹ? Ọmọ ogún ọdún ni won. Ọmọ ọdún mélòó ni àbúròò re? Ọmọ ọdún mérì...
12
13yy
Bàbáà mi, mo ní òré kan. ìyẹn dára o. Ta ni òréè re? Orúkọ rẹ ni Láńre. Ta ni bábáa Láńre ? Ojogbón Òsúndáre ni bàbáa Láńre
13
14yy
Ębli mi ni ębí Adédiran À n gbé ní ìlú Ìbàdàn ní àdúgbò ìyágànkú. Bàbá àti ìyáà mi bí ọmọ merin. Àkó̟bí wọn ń je Adéolú. Ọmọ ọdún méjìlélógbon ni won. Apòògùn sì ni won pèlú. Won ní ìyàwó. Oruko ìyàwóo won ni Gbémi. Wọn bí ọmọ méjìi, Doyin àti Yétúndé. Okùnrin ni Doyin. Doyin je ọmọ ọdún mérin. Yétúndé sì jé̟ o̟mo̟ o̟d...
14
15yy
Ębí Akinwálé Orúkọ mi ni Lolá. Orúkọ bàbáà mi ni Fémi. Orúkọ màmáà mi ni Ọláníkè̟é̟. Mo ní abúrò meta. Orúkọ won ni Jídé, Báyò àti Bùnmi. Jídé àti Báyò ni àwọn abúrò mi ọkùnrin, Bunmi sì ni àbúrò mi obìnrín. Jídé ni ọmọ kejì. Báyò ni ọmọ kẹta. Bunmi ni àbúrò mi àbígbéyìn. À ń gbé ní ìlú Èkó. Mo férànan gbogbo àwọn ẹbí ...
15
16yy
Bàbáà mi tínínrín, wọn sì dúdú. Màmáà mi sanra, wó̟n sì pupa. Wón lewà. Kì í se pé bàbáà mi búréwà o! Wón je ologbón, alááánú àti onírèlè. Wọn sì tún jé ènìyàn gíga. Màmáà mi je oníwápělé. Won kì í se onígbéraga. Wọn kò ga bli bàbáà mi. Wọn kò sì kúrú púpo. Won jé ènìyàn rere. Won sì jé̟ o̟mo̟lúwàbí ènìyàn.
16
18yy
Eélòó ni tàtàsée yín, ìyá aláta? Èwo nínúu won? Àwọn tí ó wà ni àárín yen? Náírá márùnún ni àwọn yen. Háà! Wọn ti won jù. N kò lè san náírá márùnún o. Ę jé kín san náírà méta àbò. Rárá, kò gbà. (Màmáa Tádé ń lọ.) Ó dára o. Ę wá mú u ní náírá méta àbò. Ẹ gbà. Náírá márùnún nìyío. Ò dára o. Ę gba náírà kan àti àádó̟ta kó...
18
19yy
Ę kááárò o, Màmáa Fúnmi E kááárò o, Màmáa Şadé, a à jí bí? A jíire o. Gbogbo ilé ńkó̟? A dúpé o. Dáadáà ni won wà. Bàbáa Şadé ńkó̟? Şé àlàáfíà ni won wà? A dúpé o. Bàbáa Fúnmi náà ńkó̟ o? Wọn wà o. Wọn mà ti lọ sí ìrìn àjò. Dáadáa ni wọn yóò dé o. Mo mà fé ra ata rodo, ata s̟ò̟ǹbò̟, tòmáàtì, àlùbosà, iyò àti epo pupa. ...
19
20yy
Háá Kúnlé, ki ni o wá se ní ọjà? Màmáa mí ní kín wá ra eran náírà mé̟wàá, ìręsìi náírà márùnún ààbò̟, ata rodo náírà kan, àlùbosà náírà kan, èfó̟ọ tètè̟ náírà méji. Wó̟n fún mi ní ogúnun náírà. Tí ìṣirò rẹ bá péjú, eélòó ni ó yẹ kín mú padà lọ sí ilé? Kúnlé, sé o mò̟ pé mo féràn ìṣirò! Wà á mú .....uhhhhh...... àádó̟ta...
20
21yy
Lángbé jíná o Orokún orí ebè Olóko ò gbowó Àdàlú elédé o Awùsá gbó keke bí obì Ó gbó bí orógbó Eléntú dé o. Òré ìkété dé o Ó tú sépo múyé, Ó fàtàrí napo pé bé Ómí é ń hó yeeyéè, Yeeyéè ní ń hó o Eyin omo àràbà méta Odòokun, Ę wa mu ún Yeeyéè ní ń hó o
21
22yy
Oní moínmóín gbewá gbewá Moínmoín epo Só mepo Şó mepo sìndin Moínmóín epo Şo fedé si pèlálùbó̟sà Moínmoín epo Oní dòdò oní moínmoin Oní dòdò oní moínmoin Nígbà tí ò tà ó gbé gbá kalè̟ Ę wá wò jà ní Láfíàji.
22
23yy
Wálé, báwo ni nǹkan? Dáadáa ni. Àwọn ẹbli rę ńkó̟? Dáadáa ni gbogbo won wà o. Màmáà mi ní kín máa kí ẹ. Wọn mà sé o, won kú àìgbàgbé mi. Àwọn òbli rę náà ńkó̟? Won ti jade láti àárò̟, kò sì yẹ kí wó̟n pé dé mọ. Ó ye kín dúró de won, nítorí pé ó pé tí mo ti rí wọn. Kí ni kín fi ṣe é lálejò báyìí? Èmi! Àlejò? Gbogbo ohun...
23
24yy
Kí ni orúkọ ọjà tí wọn ń ná ní àdúgbò tí a rìn kojá yen? Ojȧa Sánńgo ni. Sé ojà kan soso tí ó wà ní ìlú ìbàdàn nìyẹn ni? Rárá o! Kí ni orúkọ àwọn ọjà tí ó kù àti àwọn ohun tí a lè rí rà ní ibè? Orişirişi ojà ló wà ní ìlú Ìbàdàn yìí. Nínúu wọn ní a ti rí Qjàa Sánńgo, Ojàa Màpó, Ojà Aléṣinloyé, Ojàa Dùgbé, àti Ojà Orítam...
24
25yy
Màmá, irú oúnjẹ wo ni ẹ ní? Èbà, iyán, ọkà gidi àti fùfú. Irú obè wo ló wà? Obe ilá, égúsí, ewédú àti gbègìrì. Irú eran wo ló wà? Eran ògúnfe, màlúù àti ò̟yà. Eja ń ko? Irú eja wo ló wà? Eja sáwá, eja èpìà, eja aborí àti eja àrò. Eélòó ni ìgbákọ àmàlà kan? Ogúnun náírá. Şé ó gba náírá márùnúndínlógún? Rárá, kò gbà. Ogú...
25
26yy
Túndé, sé wàá wá sí ilé-ìwé lóla? Rárá o, nítorí pé araà mi kò yá. Orí ń fó̟ mi. Gbogbo ara ń ro mí. Şé o ní ibà ni? Ó dàbée, sugbon n kò mò. Şébí tí o bá ní ibà, wà á kàn lọ rí dókítà ní ilé-ìwòsàn ìjoba ni. Njé o mo wípé n kò féràn láti máa lọ sí ilé-ìwòsàn? Mo bèrù abéré púpò̟. Túndé, kì í ṣe gbogbo àìsàn ni ènìyàn ...
26
27yy
Bàwo ni, Felicia? Háà! Marcus, dáadáa ni. Kí ní o wá se ní láàbù? Mo wá se ȧyewoo sámpùlù ni. Hà! Hà! Şe è̟kó̟ nípa sáyéǹsì ni iwọ náà ñ kó̟ ni? Beeni. Mo ń ko nípa sáyè̟nsì. Bàó̟ló̟jì ni è̟kó̟ò̟ mi dálé lórí nítorí pé mà á fé di dókítá nígbà tí mo bá parí è̟kó̟ò̟ mi. Ó dára bée. Abájọ tí o fi tera móṣé. Á á dára o! Oo...
27
28yy
ìmótótó ló lè ségun àrùn gbogbo ìmótótó ló lè ségun àrùn gbogbo ìmó̟tótó ilé, ìmó̟tótó ara, ìmótótó oúnjẹ ìmótótó ló lè ségun àrùn gbogbo ìmótótó ló lè ségun àrùn gbogbo ìmótótó ló lè ségun àrùn gbogbo ìmó̟tótó ilé, ìmó̟tótó ara, ìmótótó oúnjẹ ìmótótó ló lè ségun àrùn gbogbo'
28
29yy
We ki o mo Gé èékánná re Jęun tó dára lásìkò Má jeun jù We ki o mo Gé èékánná re Jęun tó dára lásìkò Má jeun jù
29
30yy
Ní ilẹẹ Nàìjíríà, àpátíméèntì ni àwọn Yorùbá máa ń pè ní fúláàtì. Tí àwọn ènìyàn kò bá tí ì şetán láti kó̟ ilé, wọn máa ń rentì àpátíméèntì láti gbé. Àwọn alákowé ni wọn sáábà máa ń gbé fúláàtì. Àbúrò màmáà mi jẹ agbejó̟rò ní ìlú ìbàdàn. Wọn sì ré̟nti fúláàtì kan sí Bódìjà Tuntun. Orúkọ won ni Loya Adébímpé. Fúláàtì wọ...
30
31yy
llée wa jé ilé alájà méjì. Òpọlọpò̟ ojúlé ni ilé yìí ní. Àjà kìíní ní yàrá méjo̟, bé̟è̟ sì ni àjà kejì ní yàrá méjo pèlú. Bàbáà mi fi gbogbo yàrá méjèèjo tí ó wà ní àjà kìíní rentì fún àwọn ayálégbé. Àwọn ìdílé mérin otò̟ò̟tó̟ ni won gba àjà kìíní ní yàrá méji-méjì. Won fi yàrá kan şe yàrá ìbùsunun wọn. llé ìdáná méjì,...
31
32yy
Nínúu yàráà mi, mo ní ibùsùn, ìrò̟rí, àga, tábìlì ìkàwẻ, kó̟bó̟ò̟dù ìkáṣọsí, rédíò alágbèéká kékeré kan, kápéèti (ení àtéèká) àti béè béè lọ. Ní pálo, aga onítìmùtìmù merin ni wọn wà níbè, telifíṣàn ñlá kan, rédíò ñlá kan, aago ńlá kan àti orişirişi àwòrán ara ògiri ni ó wa níbè pèlú. Sítóòfù onígáàsì àti sítóòfù onike...
32
33yy
Nínú ilé-ìwee mi, oríşirişi nǹkan ni mo ní níbě bíi ìpara, ìparun, ìyarun, oṣẹ ìfoyín, ose ìwè, oṣẹ ìfo̟wó̟, aṣo ìnura, omi tútù, omi gbígbóná, búró̟ò̟sì, kábíné̟è̟tì, kànhìnkànhìn, tíṣù, àti àwọn nǹkan mìíràn. Ní gélé tí mo ba ti wọ inú ilé-ìwèè̟ mi, búró̟ò̟sì mi ni mo kó̟kó̟ máa ń kì mó̟lè̟ tí má á fi ọṣẹ ìfoyín sí i...
33
34yy
Tádé, njé o mò̟ pé kíláàsì márùnún ni mo ní ni simésítà yìí? Háà! Hun ùn. Tirẹ mà dára à. Kíláàsì márùnún ni èmi náà ni, pè̟lú láàbù. Mò ń se kákúló̟ò̟sì, físíìsì, è̟kó̟ èdèe Yorùbá, kémísírì àti sitatísííkì. Is̟é̟ náà wò̟ mí lórùn nítorí pe ojoojúmó̟ ni mo máa ń lọ sí láàbù. Mo ń ṣe àyèwò kan ló̟wó̟ nísinsìnyí fún ìdá...
34
35yy
Òpolopo ilé-ìwé ló wà ní tòótò̟, àmọ ti ilé-ìwée mi yàto gan-an ni. llé-ìwée mi yȧtò sí àwọn ilé- ìwé yòóku. Oro mi yìí kojá àpónlé, béè̟ kì í se àponlu. Àwọn Yorùbá ní bí a kò bá dé oko baba elomíràn wò, a kò lè mọ èyí tí ó tóbi jù nínú oko baba eni àti baba elomíràn. Èmi ti dé ilé-ìwé mìíràn, mo sì ti rí i dájú pé àj...
35
36yy
Adéńrelé dùndú Bánké gbangba konko gbàngbà Déńdè Bóláńlé alángbá àǹkárá ànfààní
36
37yy
Ìbàdàn llú ébá odan, olú ìpínlè̟ Òyó llú àwọn jagunjagun llú Lágelú àtOlúyòlé Ìlú ìbíkúnlé òun Ògúnmolá Ogun kò kóbàdàn rí Ìbàdàn ló kó gbogbo won yéye ìlú tó gbę àlejò, tó gbe oníle Ìbàdàn ló fè fè fè To kojáa Móníyà lonà Òyó Títí ó fi dé Ọmí Àdìó lónà Abéòkúta. Onídùndú lonà Ifè àti Onígàǹbàrí lonà Ìjèbú Ìbàdàn, ìlú ...
37
38yy
Fáwọ̀jí Yorùbá (Yorùbá Vowels) àlá àrà àwà àsà àdà àló àfọ̀ àdà àgbára àgà Tone practice àcà àcá àcā Àjàlá je àpèjúwé Jidé Àdé je ìyẹn Jáyé ẹwẹ̀ ẹwẹ́ ẹrẹ̀ èdè òde ọdẹ̀ èdè òṣé gẹlẹ̀ èkó Tone practice: ẹní ẹní ẹnī What is à to kìkì pro ọjẹ́ Dide dé èdè áńs. ìwé ìdẹ́ ìyàtọ̀ ìwé ìlú ìṣẹ́ ìyá ìwé ìdè Tone practice...
38
39yy
Kôñsónáõtì Yorùbá (Yorùbá Consonants) /b/ bàbá bó bèrè Bísí bàtà bò bé bèrù búburú ìbínú Tone practice bí bì bi bo bo bọ Bísí bá bábá bộ bàtà. Orin Bá a bá léni Bá a bá bánh ìwòn là á bánií sòtá mọ /d/ edá ìdàmú ìdále òòde òdėdė dárijì ìdáwó dáwó dánilójú odė ode Tone practice dé dè de dẹ edé èdè ode odę Adé dé ad...
39

summary

Textbook audio archive size: total 36M archive created: 8 July 2011

mp3 file size ======== ==== 01-yy_intro_alphabet.mp3 1.2M 02-yy_intro_consonants.mp3 757K 04-yy_intro_oral-vowels.mp3 319K 05-yy_intro_tones.mp3 620K 06-yy_ch01_l01_d01.mp3 1.6M 07-yy_ch02_l03_m01.mp3 1.1M 08-yy_ch02_l04_d01.mp3 1.5M 09-yy_ch03_l02_d01.mp3 856K 10-yy_ch03_l03_m01.mp3 635K 11-yy_ch04_l02_d01.mp3 726K 12-yy_ch04_l03_d02.mp3 492K 13-yy_ch05_l02_d01.mp3 199K 14-yy_ch05_l03_m01.mp3 1.3M 15-yy_ch05_l03_m02.mp3 556K 16-yy_ch05_l04_m03.mp3 456K 18-yy_ch06_l03_d01.mp3 502K 19-yy_ch06_l03_d02.mp3 743K 20-yy_ch06_l03_d03.mp3 1.1M 21-yy_ch06_l03_s01.mp3 201K 22-yy_ch06_l03_s02.mp3 313K 23-yy_ch07_l01_d01.mp3 1.2M 24-yy_ch07_l03_d02.mp3 1.3M 25-yy_ch07_l04_d03.mp3 1.2M 26-yy_ch08_l03_d01.mp3 1.3M 27-yy_ch09_l01_d01.mp3 1001K 28-yy_ch10_l02_s01.mp3 744K 29-yy_ch10_l02_s02.mp3 355K 30-yy_ch10_l03_m01.mp3 2.5M 31-yy_ch10_l04_m02.mp3 2.0M 32-yy_ch10_l04_m03.mp3 910K 33-yy_ch10_l04_m04.mp3 1.4M 34-yy_ch12_l02_d01.mp3 2.4M 35-yy_ch12_l03_m01.mp3 1.4M 36-yy_appx_syllabic-nasals.mp3 119K 37-yy_appx_poem.mp3 1.8M 38-yy_appx_vowels.mp3 4.1M 39-yy_appx_consonants.mp3 8.7M

Credit: Yorùbá Yé Mi: audio archive Creative Commons license Department of Middle Eastern Studeis The University of Texas at Austin

Downloads last month
58