Dataset Viewer
Auto-converted to Parquet Duplicate
diacritcs
stringlengths
1
36.7k
no_diacritcs
stringlengths
1
35.5k
Yóo dáná sun àwọn ilé àwọn oriṣa ilẹ̀ Ijipti; yóo jó wọn níná; yóo sì kó àwọn ará ìlú lọ sí ìgbèkùn; yóo fọ ilẹ̀ Ijipti mọ́ bí darandaran tíí ṣa eégbọn kúrò lára aṣọ rẹ̀, yóo sì jáde kúrò níbẹ̀ ní alaafia. Irúgbìn mìíràn bọ́ sórí àpáta. Nígbà tí ó hù, ó bá gbẹ nítorí kò sí omi. Arúgbó oǹdágbèsè, ó ní mélòó ni òun ó dùú...
Yoo dana sun awon ile awon orisa ile Ijipti; yoo jo won nina; yoo si ko awon ara ilu lo si igbekun; yoo fo ile Ijipti mo bi darandaran tii sa eegbon kuro lara aso re, yoo si jade kuro nibe ni alaafia. Irugbin miiran bo sori apata. Nigba ti o hu, o ba gbe nitori ko si omi. Arugbo ondagbese, o ni meloo ni oun o duuro san...
Ṣugbọn àwọn tí ó bá dúró de OLUWAyóo máa gba agbára kún agbára.Wọn óo máa fi ìyẹ́ fò lọ sókè bí ẹyẹ idì.Wọn óo máa sáré, agara kò ní dá wọn;wọn óo máa rìn, kò sì ní rẹ̀ wọ́n.“Serubabeli tí ó bẹ̀rẹ̀ kíkọ́ ilé Ọlọrun yìí ni yóo parí rẹ̀. Nígbà náà ni àwọn eniyan mi yóo mọ̀ pé èmi OLUWA àwọn ọmọ ogun ni mo rán ọ sí wọn. N...
Sugbon awon ti o ba duro de OLUWAyoo maa gba agbara kun agbara.Won oo maa fi iye fo lo soke bi eye idi.Won oo maa sare, agara ko ni da won;won oo maa rin, ko si ni re won.“Serubabeli ti o bere kiko ile Olorun yii ni yoo pari re. Nigba naa ni awon eniyan mi yoo mo pe emi OLUWA awon omo ogun ni mo ran o si won. Nitori na...
Alufaa yóo fi òróró tí ó kù ní ọwọ́ rẹ̀ ra orí ẹni tí wọ́n fẹ́ sọ di mímọ́. Lẹ́yìn náà, yóo ṣe ètùtù fún un níwájú OLUWA.Orílẹ̀-èdè meje ni ó parẹ́ ní ilẹ̀ Kenaani nítorí tiwọn, ó sì jẹ́ kí wọ́n jogún ilẹ̀ wọn, Nígbà tí ìparun ń bọ̀ wá bá gbogbo nǹkan báyìí, irú ìgbé-ayé wo ni ó yẹ kí ẹ máa gbé? Ẹ níláti jẹ́ eniyan ọ̀...
Alufaa yoo fi ororo ti o ku ni owo re ra ori eni ti won fe so di mimo. Leyin naa, yoo se etutu fun un niwaju OLUWA.Orile-ede meje ni o pare ni ile Kenaani nitori tiwon, o si je ki won jogun ile won, Nigba ti iparun n bo wa ba gbogbo nnkan bayii, iru igbe-aye wo ni o ye ki e maa gbe? E nilati je eniyan oto ati olufokans...
Orí tó kọ ẹrù, owó ní ńnáni.
Ori to ko eru, owo ni nnani.
Wọn óo fọ́n wọn dà sílẹ̀ ninu oòrùn, ati lábẹ́ òṣùpá ati àwọn ìràwọ̀ tí wọ́n ní ìfẹ́ sí, tí wọ́n sì sìn; àwọn ohun tí wọn ń wá kiri, tí wọn ń ṣe ìwádìí lọ́dọ̀ wọn, tí wọ́n sì ń bọ. A kò ní kó egungun wọn jọ, bẹ́ẹ̀ ni a kò ní sin wọ́n. Wọn óo dàbí ìgbọ̀nsẹ̀ lórí ilẹ̀. Ẹnu mi yóo máa sọ̀rọ̀ ìyìn OLUWA;kí gbogbo ẹ̀dá máa ...
Won oo fon won da sile ninu oorun, ati labe osupa ati awon irawo ti won ni ife si, ti won si sin; awon ohun ti won n wa kiri, ti won n se iwadii lodo won, ti won si n bo. A ko ni ko egungun won jo, bee ni a ko ni sin won. Won oo dabi igbonse lori ile. Enu mi yoo maa soro iyin OLUWA;ki gbogbo eda maa yin oruko re lae at...
Wọ́n sọ ilẹ̀ wọn di ohun ẹ̀rù ati ohun àrípòṣé títí lae.Gbogbo àwọn tí wọn bá gba ibẹ̀ kọjá ni ẹ̀rù yóo máa bà,tí wọn yóo sì máa mi orí.Ṣàánú mi, Ọlọrun, nítorí pé àwọn eniyan ń lépa mi;ọ̀tá gbógun tì mí tọ̀sán-tòru.a jẹ́ pé àrùn ẹ̀tẹ̀ gan-an ni ó wà ní ara ẹni náà. Kí alufaa pè é ní aláìmọ́; kí ó má wulẹ̀ tì í mọ́lé, ...
Won so ile won di ohun eru ati ohun aripose titi lae.Gbogbo awon ti won ba gba ibe koja ni eru yoo maa ba,ti won yoo si maa mi ori.Saanu mi, Olorun, nitori pe awon eniyan n lepa mi;ota gbogun ti mi tosan-toru.a je pe arun ete gan-an ni o wa ni ara eni naa. Ki alufaa pe e ni alaimo; ki o ma wule ti i mole, nitori pe ala...
Asán ni kí á jí ní òwúrọ̀ kutukutu,kí á tún pẹ́ títí kí á tó sùn.Asán ni kí á máa fi làálàá wá oúnjẹ;nítorí pé OLUWA a máa fún àwọn àyànfẹ́ rẹ̀ ní oorun sùn.Wọn óo di etí wọn sí òtítọ́; ìtàn àhesọ ti ara wọn ni wọn yóo máa gbọ́. Wọ́n gbé ẹran ẹbọ sísun tí wọ́n ti gé sí wẹ́wẹ́, ati orí rẹ̀ tọ̀ ọ́ lọ, ó sì sun wọ́n lórí ...
Asan ni ki a ji ni owuro kutukutu,ki a tun pe titi ki a to sun.Asan ni ki a maa fi laalaa wa ounje;nitori pe OLUWA a maa fun awon ayanfe re ni oorun sun.Won oo di eti won si otito; itan aheso ti ara won ni won yoo maa gbo. Won gbe eran ebo sisun ti won ti ge si wewe, ati ori re to o lo, o si sun won lori pepe. E yera f...
Gun orí òkè Pisiga lọ, gbé ojú sókè, kí o sì wo apá ìwọ̀ oòrùn, ati apá àríwá, ati apá gúsù, ati apá ìlà oòrùn. Ojú ni o óo fi rí i, nítorí pé, o kò ní kọjá odò Jọdani yìí sí òdìkejì. Elija tún sọ fún Eliṣa pé, “Dúró níhìn-ín nítorí pé OLUWA rán mi sí odò Jọdani.”Eliṣa dáhùn pé, “Bí OLUWA ti ń bẹ, tí ìwọ náà sì wà láày...
Gun ori oke Pisiga lo, gbe oju soke, ki o si wo apa iwo oorun, ati apa ariwa, ati apa gusu, ati apa ila oorun. Oju ni o oo fi ri i, nitori pe, o ko ni koja odo Jodani yii si odikeji. Elija tun so fun Elisa pe, “Duro nihin-in nitori pe OLUWA ran mi si odo Jodani.”Elisa dahun pe, “Bi OLUWA ti n be, ti iwo naa si wa laaye...
Bíi fìtílà ẹni ibi ni gbígbé ojú gangan ati ìgbéraga,ẹ̀ṣẹ̀ sì ni wọ́n.OLUWA kò ní fi olódodo lé e lọ́wọ́,tabi kí ó jẹ́ kí á dá olódodo lẹ́bi ní ilé ẹjọ́.N óo fọ́nnu nípa irú ọkunrin bẹ́ẹ̀. Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé n kò ní fọ́nnu nípa ara tèmi ati nípa àwọn àìlera mi. ẹran ọ̀sìn bo pápá oko bí aṣọ,ọkà bo gbogbo àfonífojì, ó sì...
Bii fitila eni ibi ni gbigbe oju gangan ati igberaga,ese si ni won.OLUWA ko ni fi olododo le e lowo,tabi ki o je ki a da olododo lebi ni ile ejo.N oo fonnu nipa iru okunrin bee. Bi o tile je pe n ko ni fonnu nipa ara temi ati nipa awon ailera mi. eran osin bo papa oko bi aso,oka bo gbogbo afonifoji, o si so jingbinni,w...
Ọlọrun sé orísun omi tí ó wà lábẹ́ ilẹ̀, ó ti àwọn fèrèsé ojú ọ̀run, òjò náà sì dá. Ramoti ati Anemu, pẹlu àwọn pápá oko àyíká wọn.Adura rẹ̀ sí Ọlọrun, ati bí Ọlọrun ṣe dá a lóhùn, àwọn ẹ̀ṣẹ̀ ati aiṣododo rẹ̀, wà ninu ìwé Ìtàn Àwọn Aríran. Bẹ́ẹ̀ náà ni gbogbo ibi tí ó kọ́ pẹpẹ ìrúbọ rẹ̀ sí, àwọn ère tí ó gbẹ́ fún Aṣera...
Olorun se orisun omi ti o wa labe ile, o ti awon ferese oju orun, ojo naa si da. Ramoti ati Anemu, pelu awon papa oko ayika won.Adura re si Olorun, ati bi Olorun se da a lohun, awon ese ati aisododo re, wa ninu iwe Itan Awon Ariran. Bee naa ni gbogbo ibi ti o ko pepe irubo re si, awon ere ti o gbe fun Asera, ati awon e...
Ẹyẹ ò lè rí omi inú àgbọn bù mu.
Eye o le ri omi inu agbon bu mu.
N óo kọrin ìfẹ́ ati ìdájọ́ òdodo,OLUWA, ìwọ ni n óo máa kọrin ìyìn sí.OLUWA, bukun àwọn ohun ìní wọn,sì jẹ́ kí iṣẹ́ ọwọ́ wọn jẹ́ ìtẹ́wọ́gbà lójú rẹ,Fọ́ egungun itan àwọn ọ̀tá wọn,tẹ̀ wọ́n ní àtẹ̀rẹ́,kí àwọn tí wọ́n bá kórìíra wọn má sì lè gbérí mọ́.”Habitual debtor who butchers a pigeon for sale.
N oo korin ife ati idajo ododo,OLUWA, iwo ni n oo maa korin iyin si.OLUWA, bukun awon ohun ini won,si je ki ise owo won je itewogba loju re,Fo egungun itan awon ota won,te won ni atere,ki awon ti won ba koriira won ma si le gberi mo.”Habitual debtor who butchers a pigeon for sale.
Ó bọ́ lọ́wọ́ oṣù ó dàràn-mọ́jú.
O bo lowo osu o daran-moju.
Ní ọjọ́ náà, ẹnu rẹ óo yà, o óo sì le sọ̀rọ̀; o kò ní ya odi mọ́. Ìwọ ni o óo jẹ́ àmì fún wọn; wọn óo wá mọ̀ pé èmi ni OLUWA.”“Mo ṣebí kọbọ meji ni wọ́n ń ta ológoṣẹ́ marun-un. Sibẹ kò sí ọ̀kan ninu wọn tí Ọlọrun fi ojú fò dá. Mose bá ranṣẹ lọ pe Datani ati Abiramu, àwọn ọmọ Eliabu, ṣugbọn wọ́n kọ̀ wọn kò wá. Gbá asà a...
Ni ojo naa, enu re oo ya, o oo si le soro; o ko ni ya odi mo. Iwo ni o oo je ami fun won; won oo wa mo pe emi ni OLUWA.”“Mo sebi kobo meji ni won n ta ologose marun-un. Sibe ko si okan ninu won ti Olorun fi oju fo da. Mose ba ranse lo pe Datani ati Abiramu, awon omo Eliabu, sugbon won ko won ko wa. Gba asa ati apata mu...
Ta ni ẹ óo wá fi mí wé,tí n óo sì dàbí rẹ̀?Èmi Ẹni Mímọ́ ni mo bèèrè bẹ́ẹ̀.Bí ìgbín ńfà, ìkaraun a tẹ̀lé é.
Ta ni e oo wa fi mi we,ti n oo si dabi re?Emi Eni Mimo ni mo beere bee.Bi igbin nfa, ikaraun a tele e.
“Bí ẹnikẹ́ni bá dẹ́ṣẹ̀ sí OLUWA nípa ṣíṣe èyíkéyìí ninu nǹkan wọnyi: kì báà jẹ́ pé ó kọ̀ láti dá ohun tí aládùúgbò rẹ̀ fi dógò pada ni, tabi pé ó ja aládùúgbò rẹ̀ lólè ni, tabi pé ó rẹ́ ẹ jẹ ni, Kí o ṣe ara rẹ ní àpẹẹrẹ rere ní gbogbo ọ̀nà. Ninu ẹ̀kọ́ tí ò ń kọ́ àwọn eniyan, kí wọn rí òtítọ́ ninu rẹ, kí wọn sì rí ìwà ...
“Bi enikeni ba dese si OLUWA nipa sise eyikeyii ninu nnkan wonyi: ki baa je pe o ko lati da ohun ti aladuugbo re fi dogo pada ni, tabi pe o ja aladuugbo re lole ni, tabi pe o re e je ni, Ki o se ara re ni apeere rere ni gbogbo ona. Ninu eko ti o n ko awon eniyan, ki won ri otito ninu re, ki won si ri iwa agba lowo re. ...
Ọgbọn la fi ńgbé ayé.
Ogbon la fi ngbe aye.
Oholibama, Ela, ati Pinoni, Pẹlu ibinu, ni mo fi fun yín ní àwọn ọba yín, ìrúnú ni mo sì fi mú wọn kúrò. Ẹ gbé gbogbo ihamọra Ọlọrun wọ̀, kí ẹ lè dúró láti dojú kọ èṣù pẹlu ọgbọ́n àrékérekè rẹ̀. Noga, Nefegi, ati Jafia, kí ọkàn mi lè máa yìn ọ́ láìdákẹ́.OLUWA Ọlọrun mi, n óo máa fi ọpẹ́ fún ọ títí lae.N óo sọ wọ́n di o...
Oholibama, Ela, ati Pinoni, Pelu ibinu, ni mo fi fun yin ni awon oba yin, irunu ni mo si fi mu won kuro. E gbe gbogbo ihamora Olorun wo, ki e le duro lati doju ko esu pelu ogbon arekereke re. Noga, Nefegi, ati Jafia, ki okan mi le maa yin o laidake.OLUWA Olorun mi, n oo maa fi ope fun o titi lae.N oo so won di ohun ti ...
N óo fọ́ ìlẹ̀kùn odi ìlú Damasku. N óo sì pa gbogbo àwọn ará àfonífojì Afeni run. Wọn óo mú ọba Betedeni lọ sí ìgbèkùn; òun ati àwọn ará Siria yóo lọ sí ìgbèkùn ní ilẹ̀ Kiri.” OLUWA ló sọ bẹ́ẹ̀. Ẹni tí ó bá fẹ́ pè ọ́ lẹ́jọ́ láti gba àwọ̀tẹ́lẹ̀ rẹ, jẹ́ kí ó gba ẹ̀wù àwọ̀lékè rẹ náà. Ta ló lè ka àwọn ọmọ ogun rẹ̀?Ta ni ì...
N oo fo ilekun odi ilu Damasku. N oo si pa gbogbo awon ara afonifoji Afeni run. Won oo mu oba Betedeni lo si igbekun; oun ati awon ara Siria yoo lo si igbekun ni ile Kiri.” OLUWA lo so bee. Eni ti o ba fe pe o lejo lati gba awotele re, je ki o gba ewu awoleke re naa. Ta lo le ka awon omo ogun re?Ta ni imole re ko tan s...
Tọkàntọkàn ni mo fi ń ṣe ìfẹ́ rẹ,má jẹ́ kí n ṣìnà kúrò ninu òfin rẹ.Ibinu rẹ pa wá run;ìrúnú rẹ sì bò wá mọ́lẹ̀.Ó ṣa igba (200) ewúrẹ́ ati ogún òbúkọ, igba (200) aguntan, ati ogún àgbò, Mo dójúlé yín láti ṣe yín ní ibi. Ibi ni n óo ṣe yín, n kò ní ṣe yín ní oore. Gbogbo àwọn ará Juda tí wọ́n wà ní Ijipti ni ogun ati ìy...
Tokantokan ni mo fi n se ife re,ma je ki n sina kuro ninu ofin re.Ibinu re pa wa run;irunu re si bo wa mole.O sa igba (200) ewure ati ogun obuko, igba (200) aguntan, ati ogun agbo, Mo dojule yin lati se yin ni ibi. Ibi ni n oo se yin, n ko ni se yin ni oore. Gbogbo awon ara Juda ti won wa ni Ijipti ni ogun ati iyan yoo...
Wọ́n bi í pé, “Olùkọ́ni, a mọ̀ pé tààrà ni ò ń sọ̀rọ̀, tí o sì ń kọ́ àwọn eniyan lẹ́kọ̀ọ́. O kì í wo ojú eniyan kí o tó sọ̀rọ̀. Ṣugbọn pẹlu òtítọ́ ni ò ń kọ́ eniyan ní ọ̀nà Ọlọrun. Nígbà tí wọn ń jẹ ẹran náà, ibinu OLUWA ru sí wọn, ó sì mú kí àjàkálẹ̀ àrùn jà láàrin wọn. Nígbà tí ẹni tí ó jẹ́ olùdarí ìsìnkú bá kó eegun...
Won bi i pe, “Olukoni, a mo pe taara ni o n soro, ti o si n ko awon eniyan lekoo. O ki i wo oju eniyan ki o to soro. Sugbon pelu otito ni o n ko eniyan ni ona Olorun. Nigba ti won n je eran naa, ibinu OLUWA ru si won, o si mu ki ajakale arun ja laarin won. Nigba ti eni ti o je oludari isinku ba ko eegun oku jade, ti o ...
Ṣugbọn àwọn tí a kà yẹ fún ayé tí ó ń bọ̀, nígbà tí àwọn òkú bá jinde, kò ní máa gbeyawo, bẹ́ẹ̀ ni wọn kò ní máa fọmọ fọ́kọ. Nítorí náà, n óo gba yín dànù kúrò ní ilẹ̀ yìí; n óo fọn yín dànù bí òkò, sí ilẹ̀ tí ẹ̀yin ati àwọn baba yín kò mọ̀ rí. Níbẹ̀ ni ẹ óo ti máa sin oriṣa, tí ẹ óo máa bọ wọ́n tọ̀sán-tòru, nítorí pé ...
Sugbon awon ti a ka ye fun aye ti o n bo, nigba ti awon oku ba jinde, ko ni maa gbeyawo, bee ni won ko ni maa fomo foko. Nitori naa, n oo gba yin danu kuro ni ile yii; n oo fon yin danu bi oko, si ile ti eyin ati awon baba yin ko mo ri. Nibe ni e oo ti maa sin orisa, ti e oo maa bo won tosan-toru, nitori pe n ko ni saa...
Ó ń ṣẹ́jú sí àwọn ará Asiria: àwọn gomina ati àwọn ọ̀gágun, àwọn ọmọ ogun tí wọ́n di ihamọra, tí wọn ń gun ẹṣin, ọdọmọkunrin ni gbogbo wọn, ojú wọn fanimọ́ra. Kó ẹrù rẹ jáde lójú wọn ní ọ̀sán gangan kí ìwọ pàápàá jáde lójú wọn ní ìrọ̀lẹ́ bí ẹni tí ń lọ sí ìgbèkùn. kí alufaa yẹ̀ ẹ́ wò, bí ọ̀gangan ibẹ̀ bá funfun díẹ̀ tí...
O n seju si awon ara Asiria: awon gomina ati awon ogagun, awon omo ogun ti won di ihamora, ti won n gun esin, odomokunrin ni gbogbo won, oju won fanimora. Ko eru re jade loju won ni osan gangan ki iwo paapaa jade loju won ni irole bi eni ti n lo si igbekun. ki alufaa ye e wo, bi ogangan ibe ba funfun die ti o dudu die,...
Ìfẹ́ kò jẹ́ ṣe nǹkan burúkú sí ẹnìkejì. Nítorí náà ìfẹ́ ni àkójá òfin.“Ọkàn rẹ balẹ̀ ninu iṣẹ́ ibi rẹ,o ní ẹnìkan kò rí ọ.Ọgbọ́n ati ìmọ̀ rẹ mú ọ ṣìnà,ò ń sọ ní ọkàn rẹ pé, ‘Èmi nìkan ní mo wà.Kò sí ẹlòmíràn lẹ́yìn mi.’Ṣílẹ̀kùn rẹ, ìwọ ilẹ̀ Lẹbanonikí iná lè jó àwọn igi kedari rẹ!Ní oṣù kẹta ni wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí kó àwọn ...
Ife ko je se nnkan buruku si enikeji. Nitori naa ife ni akoja ofin.“Okan re bale ninu ise ibi re,o ni enikan ko ri o.Ogbon ati imo re mu o sina,o n so ni okan re pe, ‘Emi nikan ni mo wa.Ko si elomiran leyin mi.’Silekun re, iwo ile Lebanoniki ina le jo awon igi kedari re!Ni osu keta ni won bere si ko awon idamewaa naa j...
Ogún ni àwọn òpó aṣọ títa, àwọn ìtẹ́lẹ̀ wọn náà sì jẹ́ ogún. Idẹ ni ó fi ṣe ìtẹ́lẹ̀ wọn, ṣugbọn fadaka ni ó fi ṣe ìkọ́ ati àwọn ọ̀pá tẹ́ẹ́rẹ́tẹ́ẹ́rẹ́ wọn. Ọlọrun ba yín sọ̀rọ̀ láti inú iná náà wá, ẹ gbọ́ ohùn rẹ̀, ṣugbọn ẹ kò rí i. Ohùn rẹ̀ nìkan ni ẹ̀ ń gbọ́. The guest does not pay homage to the chief, only to the hos...
Ogun ni awon opo aso tita, awon itele won naa si je ogun. Ide ni o fi se itele won, sugbon fadaka ni o fi se iko ati awon opa teereteere won. Olorun ba yin soro lati inu ina naa wa, e gbo ohun re, sugbon e ko ri i. Ohun re nikan ni e n gbo. The guest does not pay homage to the chief, only to the host.
Ìpín ti ẹ̀yà Bẹnjamini gẹ́gẹ́ bí iye ìdílé wọn wà ní ààrin ilẹ̀ ẹ̀yà Juda ati ti ẹ̀yà Josẹfu. Ní ọjọ́ keje ni Eliṣama ọmọ Amihudu, olórí àwọn ẹ̀yà Efuraimu mú ọrẹ tirẹ̀ wá. Nítorí náà, ẹ jẹ́ kí á máa lépa àwọn nǹkan tí ń mú alaafia wá, ati àwọn nǹkan tí yóo yọrí sí ìdàgbàsókè láàrin ara wa. Kò nílò pé a tún ń kọ̀wé s...
Ipin ti eya Benjamini gege bi iye idile won wa ni aarin ile eya Juda ati ti eya Josefu. Ni ojo keje ni Elisama omo Amihudu, olori awon eya Efuraimu mu ore tire wa. Nitori naa, e je ki a maa lepa awon nnkan ti n mu alaafia wa, ati awon nnkan ti yoo yori si idagbasoke laarin ara wa. Ko nilo pe a tun n kowe si yin nipa or...
Kirusi ọba náà kó àwọn ohun èlò inú ilé OLUWA jáde, tí Nebukadinesari kó wá sinu àwọn ilé oriṣa rẹ̀, láti Jerusalẹmu. Mose ati Aaroni bá lọ sọ́dọ̀ Farao, wọ́n sì ṣe gẹ́gẹ́ bí àṣẹ tí OLUWA pa fún wọn. Aaroni ju ọ̀pá rẹ̀ sílẹ̀ níwájú Farao ati àwọn ẹmẹ̀wà rẹ̀, ọ̀pá náà di ejò. Nígbà tí Huṣamu kú, Hadadi, ọmọ Bedadi, tí ó...
Kirusi oba naa ko awon ohun elo inu ile OLUWA jade, ti Nebukadinesari ko wa sinu awon ile orisa re, lati Jerusalemu. Mose ati Aaroni ba lo sodo Farao, won si se gege bi ase ti OLUWA pa fun won. Aaroni ju opa re sile niwaju Farao ati awon emewa re, opa naa di ejo. Nigba ti Husamu ku, Hadadi, omo Bedadi, ti o segun awon ...
Kí àwọn alufaa, àwọn ọmọ Lefi, bá wọn lọ pẹlu; nítorí àwọn ni OLUWA Ọlọrun yín yàn láti máa ṣe alufaa ati láti máa súre fún àwọn eniyan ní orúkọ OLUWA; ati pé àwọn ni OLUWA Ọlọrun yàn láti parí àríyànjiyàn ati ẹjọ́. Nígbà náà ni Israẹli sọ fún Josẹfu pé, “Àkókò ikú mi súnmọ́ etílé, ṣugbọn Ọlọrun yóo wà pẹlu rẹ, yóo sì ...
Ki awon alufaa, awon omo Lefi, ba won lo pelu; nitori awon ni OLUWA Olorun yin yan lati maa se alufaa ati lati maa sure fun awon eniyan ni oruko OLUWA; ati pe awon ni OLUWA Olorun yan lati pari ariyanjiyan ati ejo. Nigba naa ni Israeli so fun Josefu pe, “Akoko iku mi sunmo etile, sugbon Olorun yoo wa pelu re, yoo si mu...
Òkùnkùn ò mẹni ọ̀wọ̀; ó dÍfá fún “Ìwọ́ tá nìyẹn”?
Okunkun o meni owo; o dIfa fun “Iwo ta niyen”?
Mo wí ní ọkàn ara mi pé Ọlọrun ń dán àwọn ọmọ eniyan wò, láti fihàn wọ́n pé wọn kò yàtọ̀ sí ẹranko; Ẹ má mú àpò tí wọ́n fi ń ṣagbe lọ́wọ́ lọ. Ẹ má mú ẹ̀wù àwọ̀tẹ́lẹ̀ meji. Ẹ má wọ bàtà, bẹ́ẹ̀ ni kí ẹ má mú ọ̀pá lọ́wọ́. Oúnjẹ òṣìṣẹ́ tọ́ sí i. Ẹgẹ́ ò ṣákìí; ẹní bá bọ́ sábẹ-ẹ rẹ̀, a pa á kú pátá-pátá.
Mo wi ni okan ara mi pe Olorun n dan awon omo eniyan wo, lati fihan won pe won ko yato si eranko; E ma mu apo ti won fi n sagbe lowo lo. E ma mu ewu awotele meji. E ma wo bata, bee ni ki e ma mu opa lowo. Ounje osise to si i. Ege o sakii; eni ba bo sabe-e re, a pa a ku pata-pata.
Bí ẹ bá ń ṣe rere sí àwọn tí wọn ń ṣe rere si yín, kí ni fáàrí yín? Àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ pàápàá ń ṣe bẹ́ẹ̀. Bẹ́ẹ̀ ni kí á má ṣe dán Oluwa wò, bí àwọn mìíràn ninu wọn ti dán an wò, tí ejò fi ṣán wọn pa. 6. Dajúdájú A rán Musa pẹ̀lú
Bi e ba n se rere si awon ti won n se rere si yin, ki ni faari yin? Awon elese paapaa n se bee. Bee ni ki a ma se dan Oluwa wo, bi awon miiran ninu won ti dan an wo, ti ejo fi san won pa. 6. Dajudaju A ran Musa pelu
Àmì Wa (pé), 'Mu àwọn ẹ̀nìyàn
Ami Wa (pe), 'Mu awon eniyan
rẹ Jáde kúrò nínú (onírúurú)
re Jade kuro ninu (oniruuru)
òkùnkùn bọ sínú ìmọjlẹ̀, ki o sì
okunkun bo sinu imojle, ki o si
rán wọn létí àwọn ọJọ tí i ṣe ti
ran won leti awon oJo ti i se ti
Allah." Dájúdájú, àwọn Àmì f
Allah." Dajudaju, awon Ami f
bẹ nínú eléyìí fún gbogbo
be ninu eleyii fun gbogbo
onísùúrù, olùdúp$.
onisuuru, oludup$.
7. Àti pé (Kí ẹ rántí) ìgbà tí Musa
7. Ati pe (Ki e ranti) igba ti Musa
sọ fún àwọn ẹ̀nìyàn rẹ̀ pé 'Ẹ ránti
so fun awon eniyan re pe 'E ranti
ojú rere Allah lôòrí yín nígbà tí
oju rere Allah loori yin nigba ti
Òun gbà yín là kúrò lòwọ àwọn
Oun gba yin la kuro lowo awon
ẹ̀nìyàn Fir aona tí wQn n fi ìyà
eniyan Fir aona ti wQn n fi iya
búburú jẹ yín, wọn n pa àwọn
buburu je yin, won n pa awon
ọmọkùnrin yín, wọn sì n dá àwọn
omokunrin yin, won si n da awon
ọmọbìnrin yín sí; àdánwò tí ô
omobinrin yin si; adanwo ti o
lagbára ni ìwọnyí jẹ láti ẹ̀dọ
lagbara ni iwonyi je lati edo
Ohúwa yin.
Ohuwa yin.
ÌDÁ 2
IDA 2
84. (Kí ẹ sì tún rántí) ìgbà tí
84. (Ki e si tun ranti) igba ti
Olúwa yín kéde pé, 'Bí ẹ̀yin bá n
Oluwa yin kede pe, 'Bi eyin ba n
dúpẹ, dájúdájú Emi yòò. ṣe
dupe, dajudaju Emi yoo. se
àlékún oore fún yín; ṣùgbọn tí ẹ
alekun oore fun yin; sugbon ti e
bá ṣe àìmoore, (nígbà náà kí ẹ
ba se aimoore, (nigba naa ki e
mò pé) dájúdájú ìyà Mi le koko.
mo pe) dajudaju iya Mi le koko.
9, Musa sì wi pé, 'Bi ẹ̀yin pẹ̀lú
9, Musa si wi pe, 'Bi eyin pelu
àwọn tô n bẹ lòrí ilẹ̀ patapata bá
awon to n be lori ile patapata ba
ṣe àìgbàgbọ, (ẹ kò lò ṣe ìpalára
se aigbagbo, (e ko lo se ipalara
kan fún Ọlọrun); dájúdájú Allah
kan fun Olorun); dajudaju Allah
jẹ Ẹni tí Ò tô tán, Ẹni tí ìyìn to
je Eni ti O to tan, Eni ti iyin to
sí.
si.
10. Njé ìròyìn kò ha ti dé ẹ̀dò yín
10. Nje iroyin ko ha ti de edo yin
nípa àwọn tô ti wá ṣíwájú yín, bí
nipa awon to ti wa siwaju yin, bi
àwọn ẹ̀nìyàn Nuha, àwọn ìran
awon eniyan Nuha, awon iran
“Oníyẹ̀yẹ́” ni orúkọ ẹni tí ń gbéraga,tí ó sì ń ṣe mo tó báyìí-dà báyìí.Ṣugbọn ajá kò tilẹ̀ ní gbó ẹnikẹ́ni tabi ẹran ọ̀sìn kan, jákèjádò ààrin àwọn ọmọ Israẹli; kí ẹ lè mọ̀ pé OLUWA fi ìyàtọ̀ sí ààrin àwọn ará Ijipti ati àwọn ọmọ Israẹli. Àwọn kan bá lọ sọ fún àwọn ará Gasa pé Samsoni wà níbẹ̀. Wọ́n yí ilé náà po, wọ́...
“Oniyeye” ni oruko eni ti n gberaga,ti o si n se mo to bayii-da bayii.Sugbon aja ko tile ni gbo enikeni tabi eran osin kan, jakejado aarin awon omo Israeli; ki e le mo pe OLUWA fi iyato si aarin awon ara Ijipti ati awon omo Israeli. Awon kan ba lo so fun awon ara Gasa pe Samsoni wa nibe. Won yi ile naa po, won si ba de...
32.. Kí ẹ̀yin má ṣe máa pa àwọn
32.. Ki eyin ma se maa pa awon
ọmọ yín nítorí ìbẹ̀rù òṣì. Àwa là fi
omo yin nitori iberu osi. Awa la fi
pẹ̀sẹ̀ fún wọn àti fún ẹ̀yin náà
pese fun won ati fun eyin naa
pàápàá. Dájúdájú pípa wọn jẹ ẹ̀ṣẹ̀ tí
paapaa. Dajudaju pipa won je ese ti
ô tòbi.
o tobi.
33. Àti pé kí ẹ má ṣe súnmọ ìwà
33. Ati pe ki e ma se sunmo iwa
àgbẹ̀rẹ̀, dájúdájú ô: J ìwà àìmọ
agbere, dajudaju o: J iwa aimo
àti ònà búburú.
ati ona buburu.
34. Kí ẹ má sì ṣe pa ẹ̀mí tí Allah
34. Ki e ma si se pa emi ti Allah
ṣe (pípa rẹ̀) léẹ̀wọ, àyàfi. lọnà. ẹ̀tọ.
se (pipa re) leewo, ayafi. lona. eto.
Ẹni tí a bá sì pa ní ti àbòsí,
Eni ti a ba si pa ni ti abosi,
dájúdájú Àwa ti fún àròlé rẹ̀ ní àṣẹ
dajudaju Awa ti fun arole re ni ase
láti gbẹ̀san. Dájúdájú òun jẹ ẹni tí
lati gbesan. Dajudaju oun je eni ti
a ô ràn lọwọ.
a o ran lowo.
35.. Ẹ má ṣe súnmọ ohun ìní àwọn
35.. E ma se sunmo ohun ini awon
ọmọ òrukàn, àyàfi lọnà tí ô dára títí
omo orukan, ayafi lona ti o dara titi
di ìgbà tí yòò fi dàgbà; kí ẹ sì máa
di igba ti yoo fi dagba; ki e si maa
mú àdéhùn ṣẹ. Dájúdájú àdéhùn jẹ
mu adehun se. Dajudaju adehun je
ohun tí a ô nípa rẹ̀.
ohun ti a o nipa re.
36. Kí ẹ tún máa wọn òṣùnwòọn pé
36. Ki e tun maa won osunwoon pe
nígbà tí ẹ bá wọn ọỌn (fún
nigba ti e ba won oOn (fun
ẹlòmíràn) kí ẹ sì máa wọn ọn pẹ̀lú
elomiran) ki e si maa won on pelu
òṣùnwòọn àti òdiwọn tí Ô dọgba.
osunwoon ati odiwon ti O dogba.
Eléyìí ni 0 lÔore tô sì dára jù ní
Eleyii ni 0 lOore to si dara ju ni
ìgbẹ̀hìn.
igbehin.
37. Maá sì ṣe tẹ̀lé ohun tí o kò ni
37. Maa si se tele ohun ti o ko ni
ìmọ nípa rẹ̀. Dájúdájú, etí, ojú àti
imo nipa re. Dajudaju, eti, oju ati
ọkàn, gbogbo wọn la O
okan, gbogbo won la O
nípa wọn.
nipa won.
38. Ki o má ṣe máa rìn lúri ilẹ̀ ní
38. Ki o ma se maa rin luri ile ni
ti ìgbéraga, nítorí pé ìwọ kò le tẹ
ti igberaga, nitori pe iwo ko le te
ilẹ̀ dálu, bẹ̀ẹ̀ sì ni ìwọ kò le gùn
ile dalu, bee si ni iwo ko le gun
bá òkẹ̀ dọgba.
ba oke dogba.
N ò gbà! Ẹ̀yin ọkunrin nìkan ni kí ẹ lọ sin OLUWA; nítorí pé bẹ́ẹ̀ gan-an ni ẹ fẹ́ àbí?” Wọ́n bá lé wọn jáde kúrò níwájú Farao.Bẹnaya, ọmọ Jehoiada, láti ìlú Kabiseeli, jẹ́ ọmọ ogun tí ó ti ṣe ọpọlọpọ ohun ìyanu, ó pa àwọn abàmì eniyan meji ará Moabu. Ó wọ ihò lọ pa kinniun kan ní ọjọ́ kan tí yìnyín bo ilẹ̀. Dafidi bá ...
N o gba! Eyin okunrin nikan ni ki e lo sin OLUWA; nitori pe bee gan-an ni e fe abi?” Won ba le won jade kuro niwaju Farao.Benaya, omo Jehoiada, lati ilu Kabiseeli, je omo ogun ti o ti se opolopo ohun iyanu, o pa awon abami eniyan meji ara Moabu. O wo iho lo pa kinniun kan ni ojo kan ti yinyin bo ile. Dafidi ba dahun pe...
Ohun kan ṣoṣo tí ó wà ninu àpótí náà ni tabili meji tí Mose kó sibẹ ní òkè Horebu, níbi tí Ọlọrun ti bá àwọn ọmọ Israẹli dá majẹmu nígbà tí wọ́n jáde kúrò ní Ijipti. Ọba Babiloni rí i pé òun ń pèsè ohun tí ó nílò ní ojoojumọ fún un, títí di ọjọ́ ikú rẹ̀.Lẹ́yìn ọdún meji tí nǹkan yìí ṣẹlẹ̀, Absalomu lọ rẹ́ irun aguntan...
Ohun kan soso ti o wa ninu apoti naa ni tabili meji ti Mose ko sibe ni oke Horebu, nibi ti Olorun ti ba awon omo Israeli da majemu nigba ti won jade kuro ni Ijipti. Oba Babiloni ri i pe oun n pese ohun ti o nilo ni ojoojumo fun un, titi di ojo iku re.Leyin odun meji ti nnkan yii sele, Absalomu lo re irun aguntan re ni ...
End of preview. Expand in Data Studio
README.md exists but content is empty.
Downloads last month
12