score float32 1.04 1.25 ⌀ | Bemba stringlengths 9 479 ⌀ | Yoruba stringlengths 9 499 |
|---|---|---|
1.249985 | Ilyo afumya ishakwe shonse pa nse, alashitangilila, ne mpaanga shilamukonka, pantu shalishiba ishiwi lyakwe. | Nígbà tí gbogbo àwọn aguntan rẹ̀ bá jáde, a máa lọ níwájú wọn, àwọn aguntan a sì tẹ̀lé e nítorí wọ́n mọ ohùn rẹ̀. |
1.249782 | Pantu ici e cifwaikwa ku bantu bonse.' | nítorí èyí ni ojúṣe gbogbo ènìyàn. |
1.248282 | Nansha diso dyobe dyo dyabilaabila mwanda amiwa ne muyampe?' | Tabi ni oju rẹ buburu nitori emi o dara?' |
1.248227 | Ino kadi pa mwanda wenu, banwe mwamfwatakaninye biyabiya byonka, amba kifikile na mo kikadile dyalelo dino'di, kupandija bumi bwa bantu bavule." | Ní tiyín, ẹ gbèrò ibi sí mi, ṣugbọn Ọlọrun yí i pada sí rere, kí ó lè dá ẹ̀mí ọpọlọpọ eniyan tí wọ́n wà láàyè lónìí sí. |
1.248112 | Neco nkatulandikinga kubatina bantu bafwa. | bí ó bá ṣeéṣe kí n lè dé ipò ajinde ninu òkú. |
1.246975 | Ne kadi, kemwakitai muntu bu tata pano pa ntanda, mwanda Shenu i umo enka, Yewa udi mūlu. | Ẹ ma si ṣe pe ẹnikan ni baba yin ni aye: nitori Ẹnikan ni Baba yin, Ẹni Ti n bẹ ni Ọrun." |
1.246012 | Ine nde mubatisha ku menshi, lelo wene aka mubatisha ku Mupashi wa Mushilo.'" | 8Èmi ń fi omi ṣe ìtẹ̀bọmi yín, ṣùgbọ́n Òun yóò fi Ẹ̀mí Mímọ́ ṣe ìtẹ̀bọmi yín." |
1.246005 | Cinshi Nshakwatila Ifibusa? | Kí Nìdí Tí Mi Ò Fi Ní Ọ̀rẹ́ Kankan? |
1.245369 | Nalabumba uwa kumwafwa, kabili umunankwe." | Èmi yóò ṣe olùrànlọ́wọ́ tí ó rí bí i rẹ̀ fún un." |
1.2453 | "Awe nde mweba, nati, Uwacila kasesema. | Mo sọ fun yín, ó tilẹ̀ ju wolii lọ! |
1.244951 | Nomba iwe nausunga umwangashi uuwamishe ukufika na nomba!" | Iwọ ti pa ọti-waini rere titi di isisiyi! " |
1.243933 | Ukupepa kwa cine kulelenga abantu ukwikatana | Ẹ̀sìn tòótọ́ ń mú kí àwọn èèyàn wà níṣọ̀kan |
1.243179 | Ine ndemubatishisha ku menshi, lelo ena akamubatishisha ku mupashi wa mushilo.' | 8Èmi ń fi omi ṣe ìtẹ̀bọmi yín, ṣùgbọ́n Òun yóò fi Ẹ̀mí Mímọ́ ṣe ìtẹ̀bọmi yín." |
1.242044 | Ili e funde ilikalamba kabili e lya ntanshi." | Isyí ni òfin àkọ́kọ́. ' |
1.24179 | Nomba mu kubuuka kwa bafwa, akaba umukashi wa kwa nani pali balya 7? | 28 Tí ó bá di àkókò ajinde, ninu àwọn mejeeje, iyawo ta ni obinrin náà yóo jẹ́, nígbà tí ó jẹ́ pé gbogbo wọn ni wọ́n ti fi ṣe aya?" |
1.240928 | Nangu nga alomba isabi, bushe kuti amupeela insoka? | Tabi bi o bère ẹja fun a, oun yoo fun u a ejò, dipo ti a eja? |
1.240916 | kutikeni kuli shinwe Israeli. | Ẹ fetí sí Israẹli baba yín. |
1.239438 | Talapo bidi, bengidi bami bakasepelela, ino banwe mukafwijibwa bumvu. | Àwọn iranṣẹ mi yóo máa yọ̀,ṣugbọn ìtìjú yóo máa ba yín. |
1.239091 | Nkimwenepo mwadi kintu kyafwaninwe kwipailwa; nanshi nsa kumupa mfuto ne kumulekelela." | Èmi kò rí ọ̀ràn ikú lára rẹ̀: nítorí náà èmi ó nà án, èmi ó sì fi í sílẹ̀." |
1.23773 | Awe nde mweba, nati, Uwacila kasesema. | Mo sọ fun yín, ó tilẹ̀ ju wolii lọ! |
1.235854 | Bushe Umusha wa Cishinka Kabili Uwashilimuka ni Nani? | "Ta Ni Ẹrú Olóòótọ́ àti Olóye?" |
1.23498 | Uku kusesema na ko kwalifishiwepo. | Nitorina, asọtẹlẹ ti ṣetan. |
1.234921 | Kadi, Tata untumine i musapule bukamoni pa mwanda wami." | Baba tí ó rán mi níṣẹ́ ti jẹ́rìí mi. |
1.234749 | Twalishininkisha ukuti Lesa "alalambula abamufwaisha." | DRAW CLOSE TO GOD "Olùsẹ̀san fún Àwọn Tí Ń Fi Taratara Wá A" |
1.234711 | Takuli Uwingabombela Bashikulu Wakwe Babili | "Kò sí ẹni tí ó lè sin oluwa meji. |
1.234178 | Cawamapo ulya muntu nga tafyelwe." | Ìbá sàn fún ọkùnrin náà bí a kò bá bí i. " |
1.233456 | nemunena'mba, Banwe mukafwila mu bubi bwenu. | Nítorí náà, mo wí fun yín pé ẹ óo kú sinu ẹ̀ṣẹ̀ yín. |
1.233093 | Awe calengwa ukuti takuli uwalungamikilwa ku malango ku menso ya kwa Lesa; ico uwalungama mukukutetekela e ko akekalilila no mweo, pantu 'umulungami akekalila mucutetekelo'" (Abena Galatiya 3:10-11, Abena Roma 1:17). | Ó dájú pé kò sí ẹnikẹ́ni tí Ọlọrun yóo dá láre nípa òfin, nítorí a kà á pé, "Olódodo yóo wà láàyè nípa igbagbọ. |
1.232743 | "Lesa E Walemesha." - 1 Kor. | "Ọlọ́run Ń Mú Kí Ó Máa Dàgbà." - 1 Kọ́r. |
1.231737 | Abafwa balibapingwile ukulingana nefyo balecita ifyo ifyalembelwe mumabuku. | A wá bẹ̀rẹ̀ sí ṣe ìdájọ́ àwọn òkú gẹ́gẹ́ bí iṣẹ́ wọn tí ó wà ninu àwọn ìwé àkọsílẹ̀. |
1.231538 | Asambi yakwe yayile umu muzi uku kukala ivyakulya. | (Ní àkókò yìí àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ ti lọ ra oúnjẹ ninu ìlú. |
1.230389 | Alino ukuya aiteyanye ku kukosola ilandwe lisuma lya mutende, nako kuye wa nsapato ku ngazo zinu. | Tí ẹ sì ti fí ìmúrà ìyìn rere àlàáfíà wọ ẹṣẹ̀ yín ní bàtà. |
1.229509 | I binebine nemulombola'mba, umpika katabukilepo mfumwandi bukatampe, nansha yewa utuminwe kutabuka yewa umutumine bukatampe. | Mo fẹ́ kí ẹ mọ̀ dájúdájú pé: ẹrú kò ju oluwa rẹ̀ lọ, iranṣẹ kò ju ẹni tí ó rán an níṣẹ́ lọ. |
1.229504 | Uumukonkelepo ni kabalwe uwakashika kabili uwikelepo alefumya umutende pe sonde ponse. | Ẹṣin aláwọ̀ iná ló tẹ̀ lé e, ẹni tó gùn-ún sì mú àlàáfíà kúrò nínú ayé. |
1.229149 | E ico ine nangu nine Shikulu kabili Kasambilisha, nga nsambile amakasa yenu, na imwe mufwile ukulasambana amakasa. | Bí èmi Oluwa ati Olùkọ́ni yín bá fọ ẹsẹ̀ yín, ó yẹ kí ẹ máa fọ ẹsẹ̀ ẹnìkejì yín. |
1.229077 | kupwa bakamwipaya; ino mu difuku dya busatu, ukasanguka." | Ati ni ọjọ kẹta, oun yoo tun jinde. " |
1.229023 | Na lyo line, tabapunkana. | Nitorina wọn ko ṣe imudojuiwọn ara wọn. |
1.229014 | 4 Bing'we baana, a bing'we muli ba ng'wa Mulungu; niyo muli bapyeni nguno uyo ali hamo ning'we ng'wene ntaale kutinda uyo ali mu si. | 4 Ẹnyin ọmọ mi, ti Ọlọrun li ẹnyin, ẹnyin si ti ṣẹgun wọn: nitori ẹniti mbẹ ninu nyin tobi jù ẹniti mbẹ ninu aiye lọ. |
1.228493 | I mwendele mwingilo wa lupaka lwa buninge bwandi, 20 bwaasangwile nabo Kidishitu mu bafwe, wamushikatyija ku kuboko kwandi | 1:20 eyi ti o ṣe ninu Kristi, jí i kuro ninu okú ki o si Igbekale u ni ọwọ ọtún ninu awọn ọrun, |
1.228485 | Nawelengamo imiku ni miku. | Mo ti ka o lori ati lori lẹẹkansi. |
1.227908 | Mazuba oonse ijoba nelyakacikede acikombelo, bakacilikede abalo. | Ati, o ti tunmọ si o ni oru ati awọn ọjọ, o si fi gbogbo ohun ti o beere ti o ti rẹ . |
1.227892 | Elyo akalapatulula abantu nga filya kacema apatulula impaanga pakushifumya ku mbushi. | On o si yà wọn lati ọkan miiran, gẹgẹ bi oluṣọ ya awọn agutan lati ewúrẹ. |
1.226457 | Bushe Kuti Twaishiba Icine Pali Lesa? | Ṣé A Lè Mọ Ohun Tó Jẹ́ Òtítọ́ Nípa Ọlọ́run? |
1.225775 | Nikodema waipangula amba Le muntu ubwanya kubutulwa monka namani? | Nikodemu bi í pé, "Báwo ni a ti ṣe lè tún ẹni tí ó ti di àgbàlagbà bí? |
1.225396 | Yesu washilula'mba: "Muntu umo wadi na bana babidi bana-balume. | Jesu ní, "Ọkunrin kan ní ọmọ meji. |
1.225055 | le abe ufundija'ko muntu mukwabo, kwifundijapo abe mwine, | Ìwọ tí ò ń kọ́ ẹlòmíràn, ṣé o kò ní kọ́ ara rẹ? |
1.225014 | Pa kuti kasebanya naikila pali imwe, ali ne cipyu cickalamba, pa kwishibo kuti ali ne nshita inono fye." - Ukusokoloa 12:12. | 12 Ní tìtorí èyí, ẹ máa yọ̀ ṣẹ̀ṣẹ̀, ẹ̀yin ọ̀run àti ẹ̀yin tí ń gbé inú wọn!+ Ègbé+ ni fún ilẹ̀ ayé àti fún òkun,+ nítorí Èṣù ti sọ̀ kalẹ̀ wá bá yín, ó ní ìbínú ńlá, ó mọ̀ pé sáà àkókò kúkúrú+ ni òun ní." |
1.224933 | Nangu nga alomba isabi, bushe kuti amupeela insoka? | Tàbí bí ó bèèrè) ẹja, tí yóò fún un ní ejò dípò ẹja? |
1.223963 | namani muntu ne muntu motudi wivwana ludimi lwandi lotwabutwidilwe'mo? 9 Bene Pafya, | Kí ló dé tí ẹnìkọ̀ọ̀kan wa fi gbọ́ tí wọn ń sọ èdè abínibí rẹ̀? |
1.223435 | Atile: "Umupashi wa musango yu teti mu-utamfyemo kano fye kwi pepo." | Ó dá wọn lóhùn pé, "Irú èyí kò ṣe é lé jáde, àfi pẹlu adura [ati ààwẹ̀. |
1.222845 | kupwa bakamwipaya; ino mu difuku dya busatu, ukasanguka." | Ati ni ijọ kẹta, yio si jinde. " |
1.222665 | Nde mwebe cine cine, nati, umusha tacilapo pali Shikulu wakwe, nangu ni nkombe tayacilapo pa waitumine. | Mo fẹ́ kí ẹ mọ̀ dájúdájú pé: ẹrú kò ju oluwa rẹ̀ lọ, iranṣẹ kò ju ẹni tí ó rán an níṣẹ́ lọ. |
1.222063 | namani muntu ne muntu motudi wivwana ludimi lwandi lotwabutwidilwe'mo? 9 Bene Pafya, | 8 Ẽha si ti ṣe ti awa fi ngbọ́ olukuluku li ede wa ninu eyiti a bí wa? |
1.221988 | muntu ne muntu anangile monka mwamwityile Leza. | Kí olukuluku wà ní ipò tí ó wà nígbà tí a pè é láti di onigbagbọ. |
1.220904 | Na yo insoka e pa kweba umwanakashi aiti: 'Ukufwa tamwakafwe. | Ejò wí fún obìnrin náà pé, "Ẹ̀yin kì yóò kú ikúkíkú kan." |
1.22087 | Ne kadi, kemwakitai muntu bu tata pano pa ntanda, mwanda Shenu i umo enka, Yewa udi mūlu. | Ẹ má pe ẹnìkan ní 'Baba' ní ayé, nítorí ẹnìkan ṣoṣo ni Baba yín, ẹni tí ó wà ní ọ̀run. |
1.220056 | 7 Mwabi kwi'bo be na lusa, mwanda abakakwatshilwa lusa. | 7 Alabukún-fun li awọn alãnu: nitori nwọn ó ri ãnu gbà. |
1.219049 | Ne yene kombinga yeni ningeni ashihe tamu shi vulu, mu kale nombili naantu ayehe. | Ẹ sa ipá yín, níwọ̀n bí ó bá ti ṣeéṣe, láti wà ní ìrẹ́pọ̀ pẹlu gbogbo eniyan. |
1.218963 | Nga kanshi nashuka shani ica kuti nyina wa kwa Shikulu ese kuli ine? | Mo ṣe ṣe oríire tó báyìí, tí ìyá Oluwa mi fi wá sọ́dọ̀ mi? |
1.218647 | Nansha le wiivwananga na mweivwanine Ed? | Àbí bó ṣe rí lára Ed ló ṣe rí lára rẹ̀? |
1.218134 | "Bushe niwe ulya kasesema?" | "Ìwọ ni wòlíì náà bí?" |
1.218104 | " Imwe nga mwatetekela Mose, imwe nga mwalitetekela ine, pantu wene alembele palwa ine. | Bí ẹ bá gba Mose gbọ́, ẹ̀ bá gbà mí gbọ́, nítorí èmi ni ọ̀rọ̀ ìwé tí ó kọ bá wí. |
1.217875 | Takuli Uwingabombela Bashikulu Wakwe Babili | Ko si si ẹniti o le sin oluwa meji ni akoko kanna. |
1.217571 | Ifyo fine na imwe, ilyo mukamona fyonse ifi, mukeshibe ukuti ali mupepi, ali pa mwinshi." | Bẹ́ẹ̀ gan-an ni, nígbà tí ẹ bá rí gbogbo nǹkan wọnyi, kí ẹ̀yin náà mọ̀ pé àkókò súnmọ́ tòsí, ó ti dé ẹnu ọ̀nà. |
1.216543 | E ico calisuminishiwa ukucita icisuma pe Sabata." | Nítorí náà ó yẹ láti ṣe rere ní ọjọ́ ìsinmi." |
1.216303 | Umwanakashi atile: "Mukwai, mpeeniko ayo menshi." | Ó wí fún obinrin yìí pé, "Jọ̀wọ́ lọ bá mi bu omi wá kí n mu. |
1.216282 | Uzye mutaamanya ukuti nemo ndinzile ukwikala umu ng'anda yakwe Tata?' | Nitori iwọ kò mọ pe o pọndandan fun mi lati wà ninu iwọnyi ti o jẹ ti Baba mi?" |
1.216112 | Bushe na imwe kuti amusansamusha | Ǹjẹ́ ó máa tu ìwọ náà nínú? |
1.216059 | Fumenimo Muli Wene, Mwe Bantu Bandi! | "Ẹ̀yin eniyan mi, ẹ jáde kúrò níbẹ̀! |
1.215889 | Mubiike ukutemwa kwenu pa fintu fya mu mulu, te pa fintu fya pa calo. | Ẹ máa lépa àwọn ohun tí ó wà lọ́run, ẹ má lépa àwọn ohun tí ó wà láyé. |
1.21578 | (Amalumbo 55:22) Ifi e fyo ncita cila bushiku. | (Sáàmù 55:22) Ohun tí mo máa ń gbìyànjú láti ṣe lójoojúmọ́ nìyẹn. |
1.215668 | kupa, banabahesu, kuli mu latelele mutala wa bazamaisi ba ba swana sina bona, | Ẹ̀yin ará mi, ẹ kà á sí ayọ̀ gidi nígbà tí oríṣìíríṣìí ìdánwò bá dé ba yín. |
1.215458 | lusa, kadi pa mwanda wa buswe bwandi bukatampe bwaetu ̄ | Ṣugbọn nítorí ìfẹ́ ńlá tí Ọlọrun tí ó ní àánú pupọ ní sí wa, |
1.215429 | nda shi Leza kaelelepo kunyuma yoya misambo ya kipangila, ne abe mwine kakakwelelapo kunyuma. | Nítorí bí Ọlọrun kò bá dá àwọn tí ó jẹ́ bí ẹ̀ka igi láti ìpilẹ̀ṣẹ̀ sí, kò ní dá ìwọ náà sí. |
1.21496 | Penepo ku lusangukilo, le ukekalanga mukaja ani pa bano basamba-babidi? | Nígbà tí ó bá di ọjọ́ ajinde, iyawo ta ni obinrin yìí yóo jẹ́, nígbà tí ó jẹ́ pé àwọn mejeeje ni ó ti fi ṣe aya? |
1.214675 | Atile: "Ilyo Umwana wa muntu akesa, bushe akasanga icitetekelo pano isonde?" | Ṣùgbọ́n nígbà tí Ọmọ Ènìyàn bá dé yóò ha rí ìgbàgbọ́ ní ayé bí?" |
1.214536 | Kabili ifyo mwasambilile no kupokelela kuli ine, ne fyo mwaumfwile no kumona muli ine, citeni filya fine; e lyo Lesa wa mutende akaba na imwe." | Àwọn nǹkan tí ẹ̀yin ti kọ́, tí ẹ̀yin sì ti gbà, tí ẹ̀yin sì ti gbọ́, tí ẹ̀yin sì ti rí lọ́wọ́ mi, ẹ máa ṣe wọ́n: Ọlọ́run àlàáfíà yóò sì wà pẹ̀lú yín. |
1.214525 | Nga mwaishibe fintu ifi, ninshi mwalishuka nga muleficita.'" | Bí ẹ bá mọ nǹkan wọnyi, ẹ óo láyọ̀ bí ẹ bá ń ṣe wọ́n. |
1.21448 | Kakuli coko ya ka i bubebe, mi mulwalo wa ka ha u na bukiti." | Nítorí àjàgà mi rọrùn ẹrù mi sì fúyẹ́." |
1.214408 | Bushe bonse batumwa? bushe bonse ni bakasesema, bushe bonse ni bakasambilisha? bushe bonse ni bakabomba wa fisungusho? | 29 Gbogbo wọn ni iṣe aposteli bi? gbogbo wọn ni iṣe woli bi? gbogbo wọn ni iṣe olukọni bi? gbogbo wọn ni iṣe iṣẹ iyanu bi? |
1.214031 | , Luk 22:28 banwe e b. mu matompo ami | "Ẹ̀yin ni ẹ dúró tì mí ní gbogbo àkókò ìdánwò mi. |
1.213778 | Ndemweba icine cine, nati, Umusha tacila pali Shikulu wakwe, no watumwa tacila pa wamutumine. | Mo fẹ́ kí ẹ mọ̀ dájúdájú pé: ẹrú kò ju oluwa rẹ̀ lọ, iranṣẹ kò ju ẹni tí ó rán an níṣẹ́ lọ. |
1.213133 | Nomba mu kubuuka kwa bafwa, akaba umukashi wa kwa nani pali balya 7? | Ní ọjọ́ ajinde, ti ta ni obinrin náà yóo jẹ́, nígbà tí ó jẹ́ pé àwọn mejeeje ló ti fi ṣe aya? |
1.212827 | Wilaskamana pantu nine Lesa obe.nkaku kosha. | Ma ko tan kuro, nitori emi ni Ọlọrun rẹ. |
1.212677 | Lelo muzo ukabutulwe panopano ponka, a? | Ǹjẹ́ a le bí orílẹ̀-èdè kan níjọ́ kan |
1.212661 | 18 Nkisambilangapo pa banwe bonso; | 18 Emi ko sọ nipa gbogbo nyin. |
1.211211 | kupita'po wanena bana ba bwanga'mba: "Twayai monka mu Yudea." 8 Bana ba bwanga nabo | Lẹ́yìn náà ni ó ṣẹ̀ṣẹ̀ wá wí fún àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ pé, "Ẹ jẹ́ kí á tún pada lọ sí Judia. |
1.211161 | Ba Thamuud (abantu bintumwa | Thongsing Thammavong je olori orile-ede. |
1.210981 | "Mulecita ici ku Kunjibukisha" | "Ẹ máa ṣe èyí ní ìrántí mi" |
1.210561 | Akwiza pakupapa umwana umulumendo nukumwita ukuti we Yesu, pakuti we yuyo akwiza pakupoka abantu ku mbibi zyabo." | 211.21: Lk 2.21; Jh 1.29; Ap 13.23.Òun yóò sì bí ọmọkùnrin, ìwọ yóò sì pe orúkọ rẹ̀ ní Jesu, nítorí òun ni yóò gba àwọn ènìyàn rẹ̀ là kúrò nínú ẹ̀ṣẹ̀ wọn." |
1.21035 | Iwe na bana bobe mukekala pano umuyayaya'. | Àwọn ati àwọn ọmọ wọn ati àwọn ọmọ ọmọ wọn yóo máa gbé ibẹ̀ títí lae. |
1.209601 | 22 Lelo abo i Bahebelu? | 22 Hébérù ni wọ́n bí? |
1.209529 | Ino kikafika po bakakumonanga bene Edipito bakanena'mba: Uno i wandi mukaji; penepo kwipaya bakangipaya ami, nanshi abe bakakuleka mumi. | 12Nitorina yio si ṣe, nigbati awọn ara Egipti yio ri ọ, nwọn o wipe, aya rẹ̀ li eyi: nwọn o si pa mi, ṣugbọn nwọn o dá ọ si. |
1.209392 | Abafwa balibapingwile ukulingana nefyo balecita ifyo ifyalembelwe mumabuku. | Ati pe awọn okú ni idajọ nipasẹ awọn nkan wọnyẹn ti a ti kọ sinu awọn iwe naa, gẹgẹ bi iṣẹ wọn. |
1.209375 | Inga umo ishina talisangilwe mwibuku lya mweo aposwa mumulilo (Ukusokolola 20:9-15). | Bí a bá sì rí ẹnikẹ́ni ti ́a kò kọ orúkọ rẹ̀ sínú ìwé ìyè a sọ ọ sínú adágún |
1.209198 | 53 We wikolo ukuluta tata witu Ablaamu, wino wafwa? | 53 Njẹ iwọ pọju baba wa Abrahamu lọ, ẹniti o kú? |
1.209073 | Tulacingilila Imitima Yesu 37. | À Ń Dáàbò Bo Ọkàn Wa 37. |
1.208816 | Mwikeulu umo wa Leza wasapwila bakumbi amba: "Kemwakikwatwai moyo, mwanda talai! nemusapwila myanda miyampe ya nsangaji mikatampe ikekala na bantu bonso. | 10 Angẹli na si wi fun wọn pe, Má bẹ̀ru: sawò o, mo mu ihinrere ayọ̀ nla fun nyin wá, ti yio ṣe ti enia gbogbo. |
1.20871 | pano kemwalombele kintu nansha kimo mu dijina dyami. | Ẹ kò ì tíì bèèrè ohunkohun ní orúkọ mi títí di ìsinsìnyìí. |
1.20865 | Ino, enka ne nywene mine ya ku mutwe wenu i mibalwe yonso. | Ṣugbọn gbogbo irun ori nyin li a kà pé ṣanṣan. |
Bemba-Yoruba_Sentence-Pairs Dataset
This dataset contains sentence pairs for African languages along with similarity scores. It can be used for machine translation, sentence alignment, or other natural language processing tasks.
This dataset is based on the NLLBv1 dataset, published on OPUS under an open-source initiative led by META. You can find more information here: OPUS - NLLB-v1
Metadata
- File Name: Bemba-Yoruba_Sentence-Pairs
- Number of Rows: 123086
- Number of Columns: 3
- Columns: score, Bemba, Yoruba
Dataset Description
The dataset contains sentence pairs in African languages with an associated similarity score. Each row consists of three columns:
score: The similarity score between the two sentences (range from 0 to 1).Bemba: The first sentence in the pair (language 1).Yoruba: The second sentence in the pair (language 2).
This dataset is intended for use in training and evaluating machine learning models for tasks like translation, sentence similarity, and cross-lingual transfer learning.
References
Below are papers related to how the data was collected and used in various multilingual and cross-lingual applications:
[1] Holger Schwenk and Matthijs Douze, Learning Joint Multilingual Sentence Representations with Neural Machine Translation, ACL workshop on Representation Learning for NLP, 2017
[2] Holger Schwenk and Xian Li, A Corpus for Multilingual Document Classification in Eight Languages, LREC, pages 3548-3551, 2018.
[3] Holger Schwenk, Filtering and Mining Parallel Data in a Joint Multilingual Space ACL, July 2018
[4] Alexis Conneau, Guillaume Lample, Ruty Rinott, Adina Williams, Samuel R. Bowman, Holger Schwenk and Veselin Stoyanov, XNLI: Cross-lingual Sentence Understanding through Inference, EMNLP, 2018.
[5] Mikel Artetxe and Holger Schwenk, Margin-based Parallel Corpus Mining with Multilingual Sentence Embeddings arXiv, Nov 3 2018.
[6] Mikel Artetxe and Holger Schwenk, Massively Multilingual Sentence Embeddings for Zero-Shot Cross-Lingual Transfer and Beyond arXiv, Dec 26 2018.
[7] Holger Schwenk, Vishrav Chaudhary, Shuo Sun, Hongyu Gong and Paco Guzman, WikiMatrix: Mining 135M Parallel Sentences in 1620 Language Pairs from Wikipedia arXiv, July 11 2019.
[8] Holger Schwenk, Guillaume Wenzek, Sergey Edunov, Edouard Grave and Armand Joulin CCMatrix: Mining Billions of High-Quality Parallel Sentences on the WEB
[9] Paul-Ambroise Duquenne, Hongyu Gong, Holger Schwenk, Multimodal and Multilingual Embeddings for Large-Scale Speech Mining, NeurIPS 2021, pages 15748-15761.
[10] Kevin Heffernan, Onur Celebi, and Holger Schwenk, Bitext Mining Using Distilled Sentence Representations for Low-Resource Languages
- Downloads last month
- 6