score float32 1.04 1.25 ⌀ | Dyula stringlengths 10 469 ⌀ | Yoruba stringlengths 9 496 |
|---|---|---|
1.249929 | 50Ne be min fɔ n balimaw, o ye nin ye, ko adamaden gwansan te se ka Ala ka masaya sɔrɔ, fɛɛn min ye tolita ye, o fana te se ka tolibaliya sɔrɔ fewu. | Ará, ohun tí mò ń sọ ni pé ẹran-ara ati ẹ̀jẹ̀ kò lè jogún ìjọba Ọlọrun, ati pé ohun tíí bàjẹ́ kò lè jogún ohun tí kì í bàjẹ́. |
1.249785 | Loloba min be bɔ dugugwɛdafɛ, ne bena o d'a ma fana. | Emi o si fun fun u irawọ owurọ. |
1.24939 | Ne bena to n'a ye dusukasi tuma na, | èmi yóò wà pẹ̀lú rẹ̀ nínú ìpọ́njú, |
1.24902 | 24 "Nka aw nafolobatigiw, bònè bè aw ye, katuguni aw ye aw ka ɲèsuma sòrò ka ban! | "Ṣugbọn ẹ̀yin ọlọ́rọ̀ gbé,nítorí ẹ ti jẹ ìgbádùn tiyín tán! |
1.248926 | Ladili Isirayɛlidenw ma | Èyí yóo sì jẹ́ ìkìlọ̀ fún àwọn ọmọ Israẹli. |
1.248747 | 3Ni ne ye sira d'u kɔngɔtɔlaman ma, u barika bena dɛsɛ sira la, bari u dɔw bɔyɔrɔ ka jan." | Bí mo bá sọ fún wọn láti máa lọ sí ilé wọn bẹ́ẹ̀ pẹ̀lú ebi, wọn yóò dákú lójú-ọ̀nà, nítorí pé àwọn mìíràn nínú wọn ti ọ̀nà jínjìn wá." |
1.24832 | An be se ka siyɔrɔ sɔrɔ i faa ka soo wa?" | Jọ̀wọ́ wí fún mi, ǹjẹ́ ààyè wà ní ilé baba rẹ láti wọ̀ sí ní alẹ́ yìí?" |
1.248192 | U bena i ta u bolo janko i seen kana gosi kabakuru la.› " | Wọ́n óo fi ọwọ́ wọn gbé ọ sókè,kí o má baà fi ẹsẹ̀ gbún òkúta. |
1.247926 | 44 Wo rɔ, an ye bɛn kan kelen ma an ni i ɲɔɔn tɛma, sa sereya ri kɛ nde ni ile tɛma." | 44 Njẹ nisisiyi, wá, jẹ ki a bá ara wa dá majẹmu, temi tirẹ; ki o si ṣe ẹrí lãrin temi tirẹ. |
1.247855 | Sarakalasebagaw kuntigiba ye Etiyɛni ɲininga ko: 'Mɔgɔ nunu b'i jalakira koo minw na, tiɲɛn lo wa?' | Olórí Alufaa bá bi í pé, "Ṣé bẹ́ẹ̀ ni ọ̀ràn náà rí? |
1.247836 | 17 Kumakan dɔ bɔra sankolo la k'a fɔ ko: "Nin ye ne Dencɛ kanunin ye. | 17 Ohùn kan láti ọ̀run wá sì wí pé, "Èyí sì ni àyànfẹ́ ọmọ mi, ẹni tí inú mi dùn sí gidigidi." |
1.247716 | 20 Aw tun ye jurumu ka jònw ye tuma min na, aw tun ye hòrònw ye tilennenya ta fan fè. | 20 Nitori nigbati ẹnyin ti jẹ ẹrú ẹ̀ṣẹ, ẹnyin wà li omnira si ododo. |
1.247437 | Ne y'o di Lɔti kɔmɔgɔw ma." | Mo ti fi fún àwọn ọmọ Lọti ní ìní." |
1.24728 | A ka lolow fana kɛ. | Ó sì dá àwọn ìràwọ̀ pẹ̀lú. |
1.24674 | Nka ne b'a fɔ aw ye ko hali masa Sulemani ni a ta naforotigiya bɛɛ, a ma fani si don min cɛnya ka o binfiyeren kelen cɛnya bɔ. | Ṣugbọn mò ń sọ fun yín pé Solomoni pàápàá ninu ọlá rẹ̀ kò wọ aṣọ tí ó dára tó wọn. |
1.246472 | KƐWALIW 8:1919a y'a fɔ u ye ko: "Aw ka sebagaya nin dɔ di ne ma, waasa ni ne ye n bolo la mɔgɔ min kuun na, o tigi ka Nii Senuman sɔrɔ." | Ó ní, "Ẹ fún mi ní irú àṣẹ yìí kí ẹni tí mo bá gbé ọwọ́ lé, lè gba Ẹ̀mí Mímọ́. |
1.246377 | Cɛɛ y'a jaabi ko: "Jɔn lo, waasa ne ka l'a la?" | Ọkunrin náà dáhùn pé, "Alàgbà, ta ni ẹni náà, kí n lè gbà á gbọ́? |
1.246145 | U tun be to k'a fɔ ko: "Baali, an jaabi!" | Wọ́n ń wí pé, "Baali, dá wa lóhùn! |
1.245977 | 11Ni jinatɔw y'a ye tuma o tuma, u tun b'u kunbiri gwan a kɔrɔ ka pɛrɛn ko: "I ye Ala Dencɛ ye." | 11 Ati awọn ẹmi aimọ́, nigbàkugba ti nwọn ba ri i, nwọn a wolẹ niwaju rẹ̀, nwọn a kigbe soke, wipe, Iwọ li Ọmọ Ọlọrun. |
1.245959 | 36 Aw ka kè makarikèlaw ye i ko aw Fa ye makarikèla ye cogo min na. | 36 Njẹ ki ẹnyin ki o li ãnu, gẹgẹ bi Baba nyin si ti li ãnu. |
1.245571 | 21O kɔ, n tɛmɛna ka taga Siri ni Silisi jamana na. | Lẹ́yìn náà mo lọ sí agbègbè Siria ati ti Silisia. |
1.245534 | Diɲè b'a di cogo min na, ne t'a di aw ma ten dè. | Kì í ṣe bí ayé ti í fúnni ni mo fun yín. |
1.245248 | N facɛ be sii la halibi wa?" | Ṣe baba mi sì wà láààyè?" |
1.245071 | 3 Ne b'a fò aw ye ko ayi dèrè, nka ni aw ma nimisa aw ka jurumuw la, aw bèè na halaki ten. | Mò ń sọ fun yín pé bí ẹ kò bá ronupiwada, gbogbo yín ni ẹ óo ṣègbé bákan náà. |
1.244569 | 33Piyɛri y'a fɔ a ye ko: "Matigi, hali ni ne ka kan ka fara i kan u k'an don kaso la, walima u k'an faga, ne be sɔn." | Ṣugbọn Peteru dáhùn pé, "Oluwa, mo ṣetán láti bá ọ wẹ̀wọ̀n, ati láti bá ọ kú. |
1.24456 | Jɔncɛ kantigiman hakiliman ye jɔn lo ye? | Ta Ni Ẹrú Olóòótọ́ àti Olóye? |
1.244444 | 1 Sarakalasebaaw kuntigi ko: "O kow kèra ten wa?" | 1Nígbà náà ni olórí àlùfáà wí pé, "Òtítọ́ ha ni àwọn ẹ̀sùn tí wọ́ fi kàn ọ́ bí?" |
1.244324 | Nga aw ka nisɔndiya bari Ala y'aw tɔgɔ sɛbɛn a fɛ sankolo la." | Ẹ má yọ̀ ní ti pé àwọn ẹ̀mí èṣù gbọ́ràn si yín lẹ́nu; ṣugbọn ẹ máa yọ̀ nítorí a ti kọ orúkọ yín sí ọ̀run. |
1.244234 | 46"Mun na aw be ne wele Matigi, Matigi, k'a sɔrɔ ne be min fɔ aw ye, aw t'o kɛ? | 46 Ẽsitiṣe ti ẹnyin npè mi li Oluwa, Oluwa, ti ẹnyin kò si ṣe ohun ti mo wi? |
1.244196 | 35Mɔgɔ bɛɛ ben'a lɔn o seen fɛ ko aw kɛra ne ka kalandenw ye, ni aw be ɲɔgɔn kanu." | 35 Nípa èyí ni gbogbo eniyan yóo mọ pé ọmọ-ẹyìn mi ni yín, bí ẹ bá fẹràn ara yín." |
1.244119 | 9Aw kana mɔgɔ si wele ko aw facɛ dugukolo kan, bari aw Facɛ ye kelen ye, Ala min be sankolo la. | 9 Ẹ má si ṣe pè ẹnikan ni baba nyin li aiye: nitori ẹnikan ni Baba nyin, ẹniti mbẹ li ọrun. |
1.243951 | 12A ka kalandenw gwɛrɛla a la k'a fɔ a ye ko: "I m'a lɔn ko i ka kuma nin digira *Fariziɲɛw na k'u hakili ɲagami wa?" | 12 Nigbana li awọn ọmọ-ẹhin rẹ̀ wá, nwọn si wi fun u pe, Iwọ mọ̀ pe, awọn Farisi binu lẹhin igbati nwọn gbọ́ ọ̀rọ yi? |
1.243619 | 28A y'u jaabi ko: ‹Ne jugu dɔ le y'o baara kɛ.› | 28"Ó sọ fún wọn pé, 'Ọ̀tá ni ó ṣe èyí.' |
1.243425 | 11 Ai wa faaninta kɛ, wo ri kɛ an na teriya tɔɔmasere ri nde ni aile tɛma. | 11 Ẹnyin o si kọ ara nyin ni ilà; on ni yio si ṣe àmi majẹmu lãrin temi ti nyin. |
1.243405 | 3A ko: "Matigi, u y'i ka kiraw faga k'i ka sarakabɔyɔrɔw bɛɛ cɛn, ne kelenpe le tora, u fana b'a fɛ ka ne faga." | "Oluwa, wọ́n ti pa àwọn wolii rẹ, wọ́n ti wó pẹpẹ ìrúbọ rẹ, èmi nìkan ṣoṣo ni ó kù, wọ́n sì ń wá mi láti pa. |
1.243295 | 17Ne ye mɔgɔ minw ci aw fɛ, ne ye tɔnɔ dɔ sɔrɔ aw kun olu dɔ barika la wa? | 17 Emi ha rẹ́ nyin jẹ nipa ẹnikẹni ninu awọn ti mo rán si nyin bi? |
1.243146 | 7Jɔn be i ko ne? | 7 Ta ni ó dàbí ì mi? |
1.242798 | I ka kuma ye fitinɛ ye ne sen ye. | Ọ̀rọ̀ rẹ ni àtùpà fún ẹsẹ̀ mi,òun ni ìmọ́lẹ̀ sí ọ̀nà mi. |
1.242588 | Hakilitanw, aw bena faamuli kɛ waati jumɛn? | ẹ̀yin aṣiwèrè, nígbà wo ni ẹ̀yin yóò lóye? |
1.242357 | N Faa, k'a fɔ ko i ka ne kisi nin waati tɔɔrɔ ma wa? | 'Baba, gbà mí kúrò nínú wákàtí yìí'? |
1.24231 | Ala ye kanuya de jira Hadamadenw na min ɲɔgɔn tɛ yen, a kɛlen ka a Denkɛ ci o ka na sa an kosɔn. | Ọ̀nà tí Ọlọrun fi fi ìfẹ́ tí ó ní sí wa hàn ni pé ó ti rán ààyò ọmọ rẹ̀ wá sáyé kí á lè ní ìgbàlà nípasẹ̀ rẹ̀. |
1.242179 | 11 A fana gwɛnin lo ko Ala ɲakɔrɔ mɔgɔ si te se ka jati mɔgɔtilennin ye sariya barika la, bari a fɔra Ala ka kuma na ko: "Mɔgɔtilennin bena kisi lanaya barika la." | Ó dájú pé kò sí ẹnikẹ́ni tí Ọlọrun yóo dá láre nípa òfin, nítorí a kà á pé, "Olódodo yóo wà láàyè nípa igbagbọ. |
1.24215 | Nka ne b'a fɔ aw ye ko hali masa Sulemani ni a ta naforotigiya bɛɛ, a ma fani si don min cɛnya ka o binfiyeren kelen cɛnya bɔ. | Ṣugbọn mo wi fun nyin, ko ani Solomoni, ninu gbogbo ogo rẹ, ti a wọ bi ọkan ninu awọn wọnyi. |
1.242083 | I ka siko ɲafɔ e ka jɔɔnw ye, an ben'a kɔrɔ fɔ i ye." | Sọ àlá náà fún àwọn ìránṣẹ́ rẹ, awa o si fi itumọ rẹ̀ hàn. |
1.241783 | Jɔn lo be Ala ka mɔgɔw ɲɛminɛna bi? | Ta Ló Ń Darí Àwa Èèyàn Ọlọ́run Lónìí? |
1.241782 | An tɛ se ka kuma n'u ye, u fana tɛ se ka kuma n'an ye. | A ò lè bá wọn sọ̀rọ̀, àwọn náà ò sì lè bá wa sọ̀rọ̀. |
1.241744 | Aw gwɛnin lo, nga aw bɛɛ tɛ." | Ẹ̀yin mọ́, ṣugbọn kì í ṣe gbogbo yín." |
1.241592 | 69Nga, kabini sisan, Mɔgɔ Dencɛ bena sigi Setigi Ala kinibolo fɛ." | Láti àkókò yìí, Ọmọ-Eniyan yóo jókòó lọ́wọ́ ọ̀tún Ọlọrun Olodumare. |
1.241089 | 15Olu tagara yen, ka Ala daali u ye, janko u ka se ka Nii Senuman sɔrɔ, | 15 Nígbà tí wọ́n dé, wọ́n gbadura fún wọn kí wọ́n lè gba Ẹ̀mí Mímọ́, |
1.240596 | 12N balimaw, mɔgɔ minw b'aw ɲafɛ Matigi ka sira la, n'u be jija k'aw ladi, an b'aw daali ko aw ka olu jati kosɔbɛ. | Ẹ̀yin ará, à ń bẹ̀ yín pé kí ẹ máa bu ọlá fún àwọn tí ń ṣe làálàá láàrin yín, tí wọn ń darí yín nípa ti Oluwa, tí wọn ń gbà yín níyànjú. |
1.240365 | Loon min na n'aw deenw y'aw ɲininga ko nin kabakuru nunu kɔrɔ ye mun le ye, | Nígbà tí àwọn ọmọ yín bá sì bi yín léèrè pé, 'Kí ni ìtumọ̀ ìsìn yìí? |
1.240265 | Akabu yɛlɛl'a ka wotoro kɔnɔ ka taga Zizireyɛli. | Ati ki Ahabu, lọ soke, lọ si Jesreeli. |
1.23991 | 48 Aw ye o kow seerew ye. | 48 Ẹ̀yin ni ẹlẹ́rìí nǹkan wọnyi. |
1.239896 | 9 Aw ye an minè cogo min na, u yèrèw bè o lakali ko aw sònna Ala ma ka fara boliw la ka baara kè Ala sèbè ɲènama ye, 10 ka a Denkè Yesu makònò ka bò sankolo la, Ala ye o lakunun ka bò suw cèma, o ye an tila Ala ka diminya nata la. | ati bí ẹ ti ń retí Jesu, Ọmọ rẹ̀, láti ọ̀run wá, ẹni tí a jí dìde ninu òkú, tí ó yọ wá kúrò ninu ibinu tí ń bọ̀. |
1.239653 | 15Olu tagara yen, ka Ala daali u ye, janko u ka se ka Nii Senuman sɔrɔ, | Nígbà tí wọ́n dé, wọ́n gbadura fún wọn kí wọ́n lè gba Ẹ̀mí Mímọ́, |
1.239244 | Ayiwa, aw k'a lɔn fana ko ni mɔgɔ o mɔgɔ be kotilennin kɛ, k'o tigi ye Ala deen ye. | Bí ẹ bá mọ̀ pé olódodo ni, ẹ mọ̀ pé gbogbo ẹni tí ó bá ń ṣe òdodo ni ọmọ rẹ̀. |
1.239221 | - i m'a Dɔn ko denmisɛnnin 'wùlu 'sèn ka Teli nkà a tɛ 'lèru Dɔn! | 14 Ani ẹda tikararẹ̀ kò ha kọ́ nyin pe, bi ọkunrin ba ni irun gigun, àbuku ni fun u? |
1.239161 | 18Ne be barika la Ala ye, ne be kaan wɛrɛ fɔ ka tɛmɛ aw bɛɛ kan. | Mo dúpẹ́ lọ́wọ́ Ọlọrun nítorí mò ń sọ ọpọlọpọ èdè àjèjì ju gbogbo yín lọ. |
1.238923 | 64 Nga dɔw be aw cɛma minw te lara ne la." | 64 Ṣugbọn awọn kan wà ninu nyin ti kò gbagbọ́. |
1.238586 | O kama, a bɛnnin lo mɔgɔ ka koɲuman kɛ mɔgɔ ye lafiɲɛlon na." | Nítorí náà ó yẹ láti ṣe rere ní ọjọ́ ìsinmi." |
1.238581 | Nka ne b'a fɔ aw ye ko hali masa Sulemani ni a ta naforotigiya bɛɛ, a ma fani si don min cɛnya ka o binfiyeren kelen cɛnya bɔ. | Sibẹ mo sọ fun yín pé Solomoni pàápàá ninu gbogbo ìgúnwà rẹ̀ kò lè wọ aṣọ tí ó lẹ́wà bíi ti ọ̀kan ninu àwọn òdòdó yìí. |
1.23851 | 21 Yezu y'u jaabi ko: "Tiɲɛ na, ne b'a fɔ aw ye ko n'aw lara ne la, n'aw te sigasiga fewu, ne ye min kɛ torosun na, aw bena se k'o ɲɔgɔn kabakow kɛ. | 21 Jesu dahùn o si wi fun wọn pe, Lõtọ ni mo wi fun nyin, Bi ẹnyin ba ni igbagbọ́, ti ẹ kò ba si ṣiyemeji, ẹnyin kì yio ṣe kìki eyi ti a ṣe si igi ọpọtọ yi, ṣugbọn bi ẹnyin ba tilẹ wi fun òke yi pe, Ṣidi, ki o si bọ́ sinu okun, yio ṣẹ. |
1.238247 | Dugutigi b'a fɔ ko: 'Hɔnhɔn, ko: su ka don.' | Aṣọ́nà bá dáhùn, ó ní:"Ilẹ̀ ń ṣú, ilẹ̀ sì ń mọ́. |
1.238205 | 13 Min ma makari dòw la, makari tèna kè o ka kiri ko la. | 13Nítorí ẹni tí kò ṣàánú, ni a ó ṣe ìdájọ́ fún láìsí àánú; àánú ń ṣògo lórí ìdájọ́. |
1.238111 | 2"Ne y'a lɔn ko i be se koo bɛɛ la, | 2"Èmi mọ̀ pé, ìwọ lè e ṣe ohun gbogbo, |
1.237842 | A hakili b'a la ko an ye buguri ye. | ó rántí pé erùpẹ̀ ni wá. |
1.237786 | 5 Kɔni an ma sɔn ie rɔ hali waatini, sa kibaro ɲuma ri to ai jusu rɔ, kibaro ɲuma mɛn ye tuɲa ri. | Ṣugbọn a kò fi ìgbà kankan gbà wọ́n láyè rárá, kí ó má dàbí ẹni pé ọ̀rọ̀ tiwọn ni ó borí, kí òtítọ́ ìyìn rere lè wà pẹlu yín. |
1.237516 | 15N'aw balimacɛ dɔ, walima aw balimamuso dɔ fari lakolon lo, ni bii dumuni fana t'a fɛ, | Bí arakunrin kan tabi arabinrin kan bá wà ní ìhòòhò, tí kò jẹun fún odidi ọjọ́ kan, |
1.237449 | I ka kuma ye fitinɛ ye ne sen ye. | Ọrọ rẹ jẹ atupa si ẹsẹ mi ati imọlẹ si awọn ipa-ọna mi. |
1.237364 | Nuhun ye kurun kuun yɛlɛ ka filɛli kɛ, a y'a ye ko dugukolo jara. | Noa ṣí òrùlé ọkọ̀, ó yọjú wo ìta, ó sì rí i pé ilẹ̀ ti gbẹ. |
1.237337 | ‹An Faa min be sankolo la, | " 'Baba wa tí ń bẹ ní ọ̀run, |
1.237041 | Bari ne ye lonan ye i fɛ, | nítorí àlejò ni èmi lọ́dọ̀ rẹ |
1.23692 | "Abinɛri tun ka kan ka sa i n'a fɔ naloman wa? | "Ǹjẹ́ Abneri ó yẹ kí ó kú bí aṣiwèrè? |
1.236809 | Mariya ŋuuri i sɔ ni, i sunsun ka fie n niɛfɔ a. | Ẹ kí Maria, ẹni tí ó ti ṣiṣẹ́ pupọ láàrin yín. |
1.236793 | Nka jo bè di Ala ka hakilitigiya ma a ka kètaw fè." | Ṣugbọn àyọrísí iṣẹ́ Ọlọrun fihàn pé ọgbọ́n rẹ̀ tọ̀nà." |
1.236567 | ZAN 1:34 _ Ne y'o ye, o la ne ko ale lo ye Ala Deen ye." | Mo ti rí i, mo wá ń jẹ́rìí pé òun ni Ọmọ Ọlọrun." |
1.236432 | Aw tun m'a lɔn ko ne ka kan ka sɔrɔ n Faa ka soo kɔnɔ wa?" | Nitori iwọ kò mọ pe o pọndandan fun mi lati wà ninu iwọnyi ti o jẹ ti Baba mi?" |
1.236419 | Ala ka Masaya kelenpe lo bena adamadenw jigi wasa. | Ìjọba Ọlọ́run nìkan ni ìrètí tí aráyé ní. |
1.23593 | A ye koo min bɛɛ kɛ anw ye, | Fun gbogbo ohun ti o ṣe fun wa, |
1.235769 | 13 Ai ka a lɔn ko jankarɔ le ka a kɛ n sera ai wara ka kibaro ɲuma lase ai ma fɔlɔfɔlɔ. | Ṣugbọn ẹnyin mọ̀ pe ailera ara li o jẹ ki nwasu ihinrere fun nyin li akọṣe. |
1.235245 | A ka kalandenw tagara dumuni sanyɔrɔ dugu kɔnɔ. | (Ní àkókò yìí àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ ti lọ ra oúnjẹ ninu ìlú. |
1.235089 | 42 N benba Iburahima Maari Alla, n fa silanni Maari Alla mɛn yɛ kɔnin, ni wo tun ma kɛ n fɛ, sa i ra n bolokolon gbɛn a to, kɔni Alla ka n na tɔrɔya le yen. | 31:42 Ti o ba ti Ọlọrun baba mi Abrahamu, ati ẹru Isaaki ti ko ti sunmo si mi, boya nipa bayi o yoo ti rán mi lọ ni ihooho. |
1.234552 | 18 Ni mɔgɔ min y'a jigi la a kan, o tigi kisira kiti ma, nga ni min m'a jigi la a kan, o tigi jalakira ka ban bari a ma sɔn ka la Ala Dencɛ kelenpe la. | 18 Ẹniti o ba gbà a gbọ́, a ko ni da a lẹjọ; ṣugbọn a ti da ẹniti kò gbà a gbọ́ lẹjọ na, nitoriti kò gbà orukọ Ọmọ bíbi kanṣoṣo ti Ọlọrun gbọ́. |
1.234549 | O y'a sɔrɔ Yuhana tun ma bla kaso ra fɔlɔ. | (Wọn kò ì tíì ju Johanu sẹ́wọ̀n ní àkókò yìí. |
1.234331 | Mariyamu ka fɛn nyuman le nyanawoloma; mɔgɔ si tɛna se ka o bɔsi a ra." | Maria ti yan ipin ti o dara julọ, a kò sì ní gbà á lọ́wọ́ r.. " |
1.234007 | Diɲè b'a di cogo min na, ne t'a di aw ma ten dè. | Emi ko fun ọ bi aiye ṣe funni. |
1.233859 | 15A sara mɔgɔ bɛɛ le kosɔn, waasa mɔgɔ minw be nii na, olu kana taama u yɛrɛ sago la tugu, nga u k'o kɛ ale kosɔn, min sara ka kunun u ka nafa kosɔn. | Ìdí tí Kristi fi kú fún gbogbo eniyan ni pé kí àwọn tí ó wà láàyè má ṣe wà láàyè fún ara wọn, ṣugbọn kí wọ́n lè wà láàyè fún ẹni tí ó kú fún wa, tí Ọlọrun sì jí dìde. |
1.233481 | 1 Ayiwa balimaw, ne t'a fè aw ka kè ko dònbaliw ye Ni Senu ka nilifènw ta fan fè. | Ẹ̀yin ará, n kò fẹ́ kí nǹkan nípa ẹ̀bùn Ẹ̀mí Mímọ́ ṣókùnkùn si yín. |
1.233132 | 4 An bè nin kow sèbèn ka ci aw ma walisa an ka ɲagali ka dafa. | À ń kọ àwọn nǹkan wọnyi si yín kí ayọ̀ wa lè kún. |
1.232608 | Abinɛri y'a jaabi ko: "E ye jɔn ye min be pɛrɛn masacɛ kunna ten?" | Nigbana ni Abneri si dahun wipe, Iwọ tani npe ọba? |
1.232538 | A ka kalandenw y'a ɲininka o ntalen kòrò la. | Ki o si awọn ọmọ-ẹhin wi fun u pe ohun ti owe yi túmọ. |
1.232512 | 9Mɔgɔ si te soo nin kɔnɔ min ka fisa ni ne ye, a ma ne bali foyi la fɔɔ ele dama, bari e y'a ka muso ye. | Kò sí ohun tí ó fi jù mí lọ ninu ilé yìí, kò sì sí ohun tí kò fi lé mi lọ́wọ́, àfi ìwọ nìkan, nítorí pé aya rẹ̀ ni ọ́. |
1.232296 | 8A do kɛra di n'an bɛɛ b'u ka kuma mɛnna an ka kaan na? | 8 Ẽha si ti ṣe ti awa fi ngbọ́ olukuluku li ede wa ninu eyiti a bí wa? |
1.232237 | Aw te se ka nafolo kanu, ka baara kɛ Ala ye fana." | Ẹ̀yin kò lè sin Ọlọ́run àti owó papọ̀." |
1.23221 | N'a sɔrɔ o ɲiningali ka jaabili bena bari i la. | Ìdáhùn náà lè yà ọ́ lẹ́nu. |
1.231435 | 30k'a fɔ ko: ‹Cɛɛ nin ye soo lɔli daminɛ, nga a ma se k'a laban.› | Wí pé, 'Ọkùnrin yìí bẹ̀rẹ̀ sí kọ́ ilé, kò sì lè parí rẹ̀.' |
1.231357 | 24 Balimaw, bèè kelen-kelen welela k'u to cogo min na, u ka to ten Ala ɲè kòrò. | 24 Ará, ki olukuluku enia, ninu eyi ti a pè e, ki o duro ninu ọkanna pẹlu Ọlọrun. |
1.230883 | 24 Nka Ala ye minnu wele, Yahutuw ni siya wèrèw kòni, olu ɲè na, Krisita ye Ala ka sebaaya ani Ala ka hakilitigiya de ye. | ṣugbọn lójú àwọn tí Ọlọrun pè, ìbáà ṣe Juu tabi Giriki, Kristi yìí ni agbára Ọlọrun, òun ni ọgbọ́n Ọlọrun. |
1.230876 | A be se k'a fɔ sisan cogo di ko ale bɔra sankolo la?" | Ó ṣe wá sọ pé, láti ọ̀run ni òun ti sọ̀kalẹ̀ wá?" |
1.230839 | 3 A ko: "Matigi, u y'i ka kiraw faga k'i ka sarakabɔyɔrɔw bɛɛ cɛn, ne kelenpe le tora, u fana b'a fɛ ka ne faga." | "Oluwa, wọ́n ti pa àwọn wolii rẹ, wọ́n ti wó pẹpẹ ìrúbọ rẹ, èmi nìkan ṣoṣo ni ó kù, wọ́n sì ń wá mi láti pa. |
Dyula-Yoruba_Sentence-Pairs Dataset
This dataset contains sentence pairs for African languages along with similarity scores. It can be used for machine translation, sentence alignment, or other natural language processing tasks.
This dataset is based on the NLLBv1 dataset, published on OPUS under an open-source initiative led by META. You can find more information here: OPUS - NLLB-v1
Metadata
- File Name: Dyula-Yoruba_Sentence-Pairs
- Number of Rows: 102298
- Number of Columns: 3
- Columns: score, Dyula, Yoruba
Dataset Description
The dataset contains sentence pairs in African languages with an associated similarity score. Each row consists of three columns:
score: The similarity score between the two sentences (range from 0 to 1).Dyula: The first sentence in the pair (language 1).Yoruba: The second sentence in the pair (language 2).
This dataset is intended for use in training and evaluating machine learning models for tasks like translation, sentence similarity, and cross-lingual transfer learning.
References
Below are papers related to how the data was collected and used in various multilingual and cross-lingual applications:
[1] Holger Schwenk and Matthijs Douze, Learning Joint Multilingual Sentence Representations with Neural Machine Translation, ACL workshop on Representation Learning for NLP, 2017
[2] Holger Schwenk and Xian Li, A Corpus for Multilingual Document Classification in Eight Languages, LREC, pages 3548-3551, 2018.
[3] Holger Schwenk, Filtering and Mining Parallel Data in a Joint Multilingual Space ACL, July 2018
[4] Alexis Conneau, Guillaume Lample, Ruty Rinott, Adina Williams, Samuel R. Bowman, Holger Schwenk and Veselin Stoyanov, XNLI: Cross-lingual Sentence Understanding through Inference, EMNLP, 2018.
[5] Mikel Artetxe and Holger Schwenk, Margin-based Parallel Corpus Mining with Multilingual Sentence Embeddings arXiv, Nov 3 2018.
[6] Mikel Artetxe and Holger Schwenk, Massively Multilingual Sentence Embeddings for Zero-Shot Cross-Lingual Transfer and Beyond arXiv, Dec 26 2018.
[7] Holger Schwenk, Vishrav Chaudhary, Shuo Sun, Hongyu Gong and Paco Guzman, WikiMatrix: Mining 135M Parallel Sentences in 1620 Language Pairs from Wikipedia arXiv, July 11 2019.
[8] Holger Schwenk, Guillaume Wenzek, Sergey Edunov, Edouard Grave and Armand Joulin CCMatrix: Mining Billions of High-Quality Parallel Sentences on the WEB
[9] Paul-Ambroise Duquenne, Hongyu Gong, Holger Schwenk, Multimodal and Multilingual Embeddings for Large-Scale Speech Mining, NeurIPS 2021, pages 15748-15761.
[10] Kevin Heffernan, Onur Celebi, and Holger Schwenk, Bitext Mining Using Distilled Sentence Representations for Low-Resource Languages
- Downloads last month
- 8