score float32 1.04 1.25 ⌀ | Tswana stringlengths 10 499 ⌀ | Yoruba stringlengths 7 492 |
|---|---|---|
1.24874 | PARESINE e raya gore bogosi jwa gago bo neilwe Bameda le Baperesia.' | PERESINI, a ti pín ìjọba rẹ, a sì ti fún àwọn ará Mede ati àwọn ará Pasia. |
1.248267 | "O lorole mme o tla boela mo loroleng." | Erùpẹ̀ ni ọ́,o óo sì pada di erùpẹ̀. |
1.248016 | Letsatsi lengwe le lengwe le lekanwe ke bosula jwa lone." | Búburú ti ọjọ́ kọ̀ọ̀kan tó fún un. |
1.247415 | Le gona ga ba nke ba tlhola ba kgaogana go nna dipuso tse pedi. | Wọn kò ní jẹ́ orílẹ̀-èdè meji mọ́; wọn kò ní pín ara wọn sí ìjọba meji mọ́. |
1.246885 | 19O fa ba mo tshabang ho ratwang ke bona, o utlwa mehoo ya bona, mme o a ba lopolla. | 19 Yio mu ifẹ awọn ti mbẹ̀ru rẹ̀ ṣẹ: yio gbọ́ igbe wọn pẹlu, yio si gbà wọn. |
1.246592 | Ha re tsebe ya ileng a kenya tjhelete ya rona ka mekotleng ya rona." | A kò mọ ẹni tí ó dá owó wa pada sinu àpò wa. |
1.245156 | "Go tla tlhomama ntlo ya gago le bogosi ba gago ka | Ati ile rẹ ati ijọba rẹ yio si wa ni estab- |
1.245118 | 10Ditjhaba tsohle tsa lefatshe di tla elellwa hore o bitswa ka lebitso la Morena, mme di tla o tshaba. | 10 Gbogbo enia aiye yio si ri pe orukọ OLUWA li a fi npè ọ; nwọn o si ma bẹ̀ru rẹ. |
1.243465 | Iseraele, ga ke go lebale! | ìwọ Israẹli, Èmi kì yóò gbàgbé rẹ. |
1.242345 | Gonne ke monna mogolo, le mosadi wa me o tsofetse." | Nitori emi agbalagba, iyawo mi si ti di arugbo. " |
1.241999 | 3Menono le maruo di ka tlung ya hae, | 3Ọlá àti ọrọ̀ yóò wà nínú ilé rẹ̀; |
1.241804 | Mme ditšhaba tsotlhe di tla phuthelwa fa pele ga gagwe, mme o tla kgaoganya batho mongwe mo go yo mongwe, fela jaaka modisa a kgaoganya dinku le dipodi. | Gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè yóo péjọ níwájú rẹ̀, yóo wá yà wọ́n sọ́tọ̀ọ̀tọ̀, bí olùṣọ́-aguntan tíí ya àwọn aguntan sọ́tọ̀ kúrò lára àwọn ewúrẹ́. |
1.241396 | Ke mang yo o lo kgoreleditseng gore lo se utlwe boammaaruri? 8 Tlhotlheletso eo ga e tswe mo go ene yo o lo bitsang. | Ta ni dí yin lọ́wọ́ láti ṣe ìgbọ́ràn sí òtítọ́? 8Ìyípadà yìí kò ti ọ̀dọ̀ ẹni tí ó pè yín wá. |
1.240812 | 29Jesu a mo raya a re: "Tsamaya ka ntlha ya lefoko leo; modemone o dule mo go morwadio." | 29 O si wi fun u pe, Nitori ọ̀rọ yi, mã lọ; ẹmi ẹ̀ṣu na ti jade kuro lara ọmọbinrin rẹ. |
1.240666 | Ke tlile go mo direla mothusi, gore e nne motlatsi wa gagwe." | Èmi yóò ṣe olùrànlọ́wọ́ tí ó rí bí i rẹ̀ fún un." |
1.240461 | 3Menono le maruo di ka tlung ya hae, | 3 Ọlá àti ọrọ̀ yóò wà nínú ilé rẹ̀; |
1.240271 | Le ka motlha a ka se re latlhe jaaka monna wa me a dirile." | Kò sì ní pa wá tì láé bí ọkọ mi ṣe pa wá tì." |
1.239591 | Empa ya itshepetseng nna o tla ja lefa la lefatshe, a rue thaba ya ka e halalelang. | Ṣugbọn ẹniti o ni o ni igbagbo ninu mi yio jogún ilẹ ayé ati ki o yoo jogun oke mimọ mi. |
1.239171 | "Tswang mo go Ene, Batho ba Me" | "Ẹ̀yin eniyan mi, ẹ jáde kúrò níbẹ̀! |
1.239122 | Tsena mo boipelong jwa mong wa gago." | Wọ inu didùn ti oluwa rẹ. ' |
1.238735 | ya entseng tse kgolo Egepeta, | ẹni tí ó ti ṣe ohun ńlá ní Ejibiti, |
1.238595 | 8Ba se ke ba tshwana le bo-ntata bona, | 8 Kí wọn kí ó má ṣe dàbí àwọn baba ńlá wọn, |
1.238539 | Ga ke a bona molato ope o o tshwanetseng loso mo go ene; ka moo ke tla mo watlhaya ke be ke mo golola." | Èmi kò rí ọ̀ràn ikú lára rẹ̀: nítorí náà èmi ó nà án, èmi ó sì fi í sílẹ̀." |
1.237555 | Ba ya kwa motseng kwa monna wa Modimo a leng teng. | Bẹ̃ni nwọn si lọ si ilu na nibiti ẹni Ọlọrun nã gbe wà. |
1.236702 | 7A ba araba a re: "Ga go a lo tshwanela go itse metlha gongwe dinako tse Rara o di beileng ka thata ya gagwe. | Ó dá wọn lóhùn pé, "Kì í ṣe tiyín láti mọ àkókò tabi ìgbà tí Baba ti fi sí ìkáwọ́ ara rẹ̀ nìkan ṣoṣo. |
1.23587 | Jwale Aborame a mo nea karolo e le nngwe ho tse leshome tse hapilweng.+ | Abramu sì fún un ní ìdámẹ́wàá ohun gbogbo. |
1.235626 | 11ya neng a se na thuso ho wena pele, empa jwale o na le thuso ho wena le ho nna, mme ke mo kgutlisetsa ho wena. | 11 Nígbà kan rí, kò wúlò fún ọ, ṣùgbọ́n ní báyìí, ó ti wúlò fún ọ àti fún èmi pàápàá. |
1.235535 | 8Yaba ke utlwa lentswe la Morena le re: "Ke tla roma mang? | Mo wá gbọ́ ohùn OLUWA ó ní, "Ta ni kí n rán? |
1.234793 | 10Morena Modimo wa lona o lo atisitse; bonang, kajeno lo kana ka dinaledi tsa legodimo ka bontsi. | 10Olúwa Ọlọ́run yín ti sọ yín di púpọ̀ lónìí, ẹ̀yin sì ti pọ̀ bí ìràwọ̀ ní ojú ọ̀run. |
1.234562 | 37Ba mo fitlhela, ba mo raya ba re: "Botlhe ba a go batla." | 37 Nígbà tí wọ́n sì rí I, wọ́n sọ fún wí pé, "Gbogbo ènìyàn ń wá ọ!" |
1.234455 | A ga ke a go laola? | Emi ko fi aṣẹ fun ọ? |
1.234176 | 28PARESINE ke ho re: Mmuso wa hao o arotswe, o neilwe Bamede le Maperesiya." | PERESINI, a ti pín ìjọba rẹ, a sì ti fún àwọn ará Mede ati àwọn ará Pasia. |
1.23371 | 11yena eo pele e neng a se na thuso ho wena, empa jwale ya nang le thuso ho rona ba babedi. | 11Nígbà kan rí, kò wúlò fún ọ, ṣùgbọ́n ní báyìí, ó ti wúlò fún ọ àti fún èmi pàápàá. |
1.233305 | mongwe le mongwe wa rona a utlwa ba bua mo puong ya gagwe | Kí ló dé tí ẹnìkọ̀ọ̀kan wa fi gbọ́ tí wọn ń sọ èdè abínibí rẹ̀? |
1.233225 | A ga ke a go laola? | Ti mo ti ko paṣẹ fun ọ? |
1.232557 | Morafe wa ga eno le baperesiti ba bagolo ba go nneetse; o dirileng?" | Àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè rẹ, àti àwọn olórí àlùfáà ni ó fà ọ́ lé èmi lọ́wọ́: kín ní ìwọ ṣe?" |
1.232365 | 17Mme fa Keresete a sa tsosiwa, tumelo ya lona e tla bo e le lefela, lo tla bo lo sa ntse lo le mo maleong a lona. | Bí a kò bá sì jí Kristi dìde, a jẹ́ pé lásán ni igbagbọ yín, ẹ sì wà ninu ẹ̀ṣẹ̀ yín sibẹ. |
1.232197 | ga go ope yo o batlang Modimo. | kò sí ẹni tí ó ń wá Ọlọ́run. |
1.232021 | Morafe wa ga eno le baperesiti ba bagolo ba go nneetse; o dirileng?" | Awọn orilẹ-ède rẹ, ati awọn olori alufa li o fà ọ le emi lọwọ: kini iwọ ṣe? |
1.230958 | Le gona ga re na boswa mo go morwa Isai. | bẹ́ẹ̀ ni àwa kò ni ìní nínú ọmọ Jese! |
1.23049 | 3Ke lo raya ke re: Nnyaya; mme fa lo sa sokologe, le lona lo tla nyelela jalo lotlhe. | Mò ń sọ fun yín pé bí ẹ kò bá ronupiwada, gbogbo yín ni ẹ óo ṣègbé bákan náà. |
1.230479 | mme tsela e isang kgotsong, ha ba e tsebe. | Ọ̀nà àlàáfíà ni wọn kò sì mọ̀:" |
1.230289 | Metse yohle ya Baamone o ne a ye a e etse jwalo. | Bẹ heli o ṣe si gbogbo awọn ara ilu awọn ọmọ Ammoni. |
1.230116 | o gopola, fa re le lorole. | ó rántí pé erùpẹ̀ ni wá. |
1.229955 | "Mme fa Keresete a sa tsosiwa, tumelo ya lona ke lefela, lo sa ntse lo le mo dibeng tsa lona. | Bí a kò bá sì jí Kristi dìde, a jẹ́ pé lásán ni igbagbọ yín, ẹ sì wà ninu ẹ̀ṣẹ̀ yín sibẹ. |
1.229928 | 26 Tsone ka botsone di tla nyelela, mme wena ka bowena o tla nna o eme;+ | 26Wọn yóò ṣègbé, wọn yóò parun, ṣùgbọ́n ìwọ yóò wà; |
1.229717 | A kampo o jele setlhare se ke go laetseng ka re: O se ka wa se ja?" | Àbí o ti jẹ ninu èso igi tí mo pàṣẹ fún ọ pé o kò gbọdọ̀ jẹ? |
1.229389 | Wena Juda, ke etse jwang ka wena? | Kí ni kí n ti ṣe ọ́ sí, ìwọ Juda? |
1.229031 | 24 [...]Ebong rona, ba o re biditseng, eseng mo Bajuteng fela, mme le mo Baditshabeng? | 9:24 Ati ki o jẹ pẹlu awon ti wa ti o ti tun npe ni, ko nikan lati larin awọn Ju, sugbon ani ninu awọn Keferi, |
1.22898 | Josefa o lemoga bomogolowe mme bone ga ba mo lemoge. | Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé Josẹfu mọ̀ dájú pé àwọn arakunrin òun ni wọ́n, wọn kò mọ̀ ọ́n. |
1.228882 | kgatlhanong) fa gare ga gago le mosadi le fa gare ga losika lwa | sí àárín ìwọ àti obìnrin náà, |
1.228485 | Noa o Dumela mo Modimong | Nóà Ní Ìgbàgbọ́ Nínú Ọlọ́run |
1.228429 | A Moatlhodi wa lefatshe lotlhe ga a tle go dira se se siameng?" | Ìwọ onídàájọ́ gbogbo ayé kò ha ní ṣe ẹ̀tọ́ bí? |
1.228235 | 30Ke gona ka moo go leng ba bantsi mo go lona ba ba bokoa le ba ba lwalang; ba bantsi ba robetse. | Nítorí èyí ni ọpọlọpọ ninu yín ṣe di aláìlera ati ọlọ́kùnrùn, tí ọpọlọpọ tilẹ̀ ti kú. |
1.227829 | Ditsela tsa hao di lokile, ke tsa nnete, wena Kgosi ya ditjhaba. | Òdodo ati òtítọ́ ni àwọn iṣẹ́ ọnà rẹ,Ọba àwọn orílẹ̀-èdè. |
1.22738 | LUKA 10:18 Mme Are ho bona, ke bone Satane a theoha Lehodimong jwalo ka lehadima. | 10:18 O si wi fun wọn pe: "Mo n wo bi Satani ti ṣubu bi manamana lati ọrun. |
1.226976 | , Mat 16:26 se motho a. gore a bone botshelo? | Tàbí kí ni ènìyàn yóò fi ṣe pàsípàrọ̀ ẹ̀mí rẹ̀? |
1.226786 | Baperofeti ba maaka ba tla nna gone mme ba tla tsietsa ba le bantsi. | Ọpọlọpọ àwọn wolii èké ni yóo dìde, wọn yóo tan ọpọlọpọ jẹ. |
1.226679 | 27"Empa na ruri Modimo o tla hle a ahe lefatsheng? | 27 "Ṣùgbọ́n Ọlọ́run yóò ha máa gbé lórí ilẹ̀ ayé+ ní tòótọ́ bí? |
1.226226 | 32Ene a ba raya a re: "Ke na le sejo se ke se jang, se lo sa se itseng." | 32 Ṣugbọn o wi fun wọn pe, emi li onjẹ lati jẹ, ti ẹnyin kò mọ̀. |
1.226126 | 29Ya re a sena go bua jalo, Bajuta ba tsamaya, ba le mo kganetsanyong e kgolo. | 29 Nígbà tí ó ti sọ ọ̀rọ̀ wọ̀nyí fún wọn tan, àwọn Júù lọ, wọ́n bá ara wọn jiyàn púpọ̀." |
1.226103 | 43Wa ga eno o se ka wa mo laola ka bopeloethata, mme o boife Modimo wa gago. | 43 Iwọ kò gbọdọ fi irorò sìn i; ṣugbọn ki iwọ ki o bẹ̀ru Ọlọrun rẹ. |
1.225583 | 'Morafe o, o ntlotla ka melomo, | " 'Àwọn ènìyàn wọ̀nyí fi ẹnu wọn bu ọlá fún mi |
1.225412 | Lona masilo, lo tla tlhalefa leng? | Ẹ̀yin òmùgọ̀, nígbà wo ni ẹ óo gbọ́n? |
1.225352 | 24Modimo ke Moya: ba o rapelang e ka kgona ba rapele ka moya le ka nnete. | 24 Ẹmí li Ọlọrun: awọn ti o ba foribalẹ ki o mã sìn ni ẹmí ati otitọ. |
1.22535 | 39 Mme thato ya yo o nthomileng ke go re, botlhe ba o ba nneileng ke se ka ka latlhegelwa ke ope wa bone, mme bogolo ke be ke ba tsose ka letsatsi la bofelo. | Èyí ni ìfẹ́ ẹni tí ó rán mi níṣẹ́, pé kí n má ṣe sọ ẹnikẹ́ni nù ninu àwọn tí ó fi fún mi, ṣugbọn kí n jí wọn dìde ní ọjọ́ ìkẹyìn. |
1.225247 | rekilwe ka tlhwatlhwa e kgolo; galaletsang he Modimo ka | Iyebíye ni Ọlọrun rà yín, nítorí náà, ẹ fi ara yín yin Ọlọrun. |
1.225227 | Mme wena e re o sena go sokologa, o tiise bakaulengwe ba gago." | tí ìwọ bá sì padà bọ̀sípò, mú àwọn arákùnrin rẹ lọ́kàn le." |
1.224814 | 9 Jwalo kaha mahodimo a phahametse lefatshe, le tsela tsa hae jwalo ho tsa lona, le mehopolo ya Hae jwalo hoya lona. | Bí ọ̀run ṣe ga ju ayé lọ,bẹ́ẹ̀ ni ọ̀nà mi ga ju ọ̀nà yín,tí èrò mi sì ga ju èrò yín. |
1.224464 | Jaaka go kwadilwe ga twe: "Kana di dintle jang ne dinao tsa bone ba ba rerang mafoko a a thabisang a a molemo!" | Gẹgẹ bi a ti kọ ọ pe: "Bawo ni awọn ẹsẹ ti awọn ti n waasu ihinrere ti alafia, awọn ti o mu awọn ayọ ohun rere wa!" |
1.224423 | 'Dirang se e le go Nkgopola' | "Ẹ máa ṣe èyí ní ìrántí mi" |
1.224295 | 24 [...]A motho yo o bosula yo ke leng ena! ke mang yo o tla nkgololang mo mmeleng wa loso lo? | 24 Emi ẹni òṣi! tani yio gbà mi lọwọ ara ikú yi? |
1.224221 | , Mat 16:26 se motho a. gore a bone botshelo? | Tabi kí ni eniyan lè fi dípò ẹ̀mí rẹ̀? |
1.223555 | Ke tla tlhokomelwa ke mang fa ke setse ke tsofetse?' | Tí èmi náà bá dàgbà, ta ló máa tọ́jú mi? |
1.223529 | "A o Nthata go Feta Tseno?" | "Ìwọ Ha Nífẹ̀ẹ́ Mi Ju Ìwọ̀nyí Lọ Bí?" |
1.2234 | " 'Morafe o, o ntlotla ka melomo, | " 'Àwọn ènìyàn wọ̀nyí fi ẹnu wọn bu ọlá fún mi |
1.223255 | A araba a re: "Ke tla tuka bogale ka tshwanelo go fitlha losong." | Òun sì wí pé, "Mo ni ẹ̀tọ́, o tọ́ fún mi láti bínú títí dé ikú." |
1.223085 | Ka jalo, o se ka wa dira motho yo mongwe selo se se ntseng jalo! | Ìwọ náà, má ṣe bẹ́ẹ̀ fún ẹlòmíì! |
1.223043 | Ke a lo roma, jaaka Rara a nthomile." | Gẹ́gẹ́ bí baba ti rán mi níṣẹ́, bẹ́ẹ̀ ni mo rán yín. |
1.22298 | Metse yohle ya Baamone o ne a ye a e etse jwalo. | Ki o si ṣe si gbogbo awọn ilu ti awọn ọmọ Ammoni. |
1.222978 | Morena a re: "Tjhe, o ile wa tsheha." | Ṣùgbọ́n OLúWA wí fún un pé, "Dájúdájú ìwọ rẹ́rìn-ín." |
1.222912 | 52e seng morafe oo fela, mme le gona e le gore a phuthe bana ba Modimo ba ba faladitsweng, a ba kopanye. | Kì í wá ṣe fún orílẹ̀-èdè wọn nìkan, ṣugbọn kí àwọn ọmọ Ọlọrun tí ó fọ́nká lè papọ̀ di ọ̀kan. |
1.222509 | Weine le bojalwa ga ke a di nwa, mme ke tsholotse tsa pelo ya me fa pele ga Morena. | Èmi kò mu ọtí wáìnì tàbí ọtí líle; Èmi ń tú ọkàn mi jáde sí Olúwa ni. |
1.222237 | Lentswe la Hao ke lebone la maoto aka, le nkgantshetsang tsela. | Ọrọ rẹ jẹ fitila si ẹsẹ mi, ati imọlẹ si ọna mi. |
1.222187 | Morena a mo fetola a re: "Saulo o tla tla." | "OLUWA sì dáhùn pé, "Saulu yóo wá. |
1.222086 | Go ka bo go le botoka mo go ene, fa a ka bo a se ka a tsalwa." | Ìbá sàn fún ọkùnrin náà bí a kò bá bí i. " |
1.222058 | 39Mme thato ya yo o nthomileng ke go re, botlhe ba o ba nneileng ke se ka ka latlhegelwa ke ope wa bone, mme bogolo ke be ke ba tsose ka letsatsi la bofelo. | Èyí ni ìfẹ́ ẹni tí ó rán mi níṣẹ́, pé kí n má ṣe sọ ẹnikẹ́ni nù ninu àwọn tí ó fi fún mi, ṣugbọn kí n jí wọn dìde ní ọjọ́ ìkẹyìn. |
1.221986 | 19Mme re bona, fa ba paletswe ke go tsena ka ntlha ya go sa dumeleng. | 19 Awa si ri pe nwọn kò le wọ̀ inu rẹ̀ nitori aigbagbọ́. |
1.221789 | Le bokgaitsadie ba fano le rona, ga ke re?" | Àwọn arábìnrin rẹ̀ gbogbo ha kọ́ ni ó ń bá wa gbé níhìn-ín yìí?" |
1.221035 | Gonne lo tshubile molelo wa bogale jwa me o o tukang ka bosakhutleng." | Nitoriti iwọ ti da iná ni inu mi; yio jo, ani titi ayeraye. " |
1.220991 | thuso ya me e tla tswa kae? | níbo ni ìrànlọ́wọ́ mi yóò ti wá |
1.220847 | 17Mme ekare ha Kreste a sa ka a tsoha, tumelo ya lona ke lefeela, mme le sa le dibeng tsa lona. | Bí a kò bá sì jí Kristi dìde, a jẹ́ pé lásán ni igbagbọ yín, ẹ sì wà ninu ẹ̀ṣẹ̀ yín sibẹ. |
1.220748 | "Ane a teketela khotsi awe kana mme awe o fanela u vhulawa. | "Ẹnikẹ́ni tí ó bá gbé baba tabi ìyá rẹ̀ ṣépè, pípa ni kí wọ́n pa á. |
1.220592 | 8Basiami ba tla bona, ba boifa; | 6 Àwọn olódodo yóò rí, wọn yóò sì bẹ̀rù |
1.2199 | 41 Yo o tsholang moporofeti, ka e le moporofeti, o tla bona tuelo ya moporofeti; le yo o tsholang mosiami, ka e le mosiami, o tla bona tuelo ya mosiami. | 41 Ẹniti o ba gbà wolĩ li orukọ wolĩ, yio jẹ ère wolĩ; ẹniti o ba si gbà olododo li orukọ olododo yio jẹ ère olododo. |
1.219896 | Jwale wena, ha o se o bakile, o matlafatse bana beno." | tí ìwọ bá sì padà bọ̀sípò, mú àwọn arákùnrin rẹ lọ́kàn le." |
1.219748 | Ha eo a etla, o tla kgodisa lefatshe ka tsa sebe, le ka tsa toka, le ka tsa kahlolo; | Nígbà tí ó bá dé, yóo fi han aráyé pé wọ́n ti ṣìnà ninu èrò wọn nípa ẹ̀ṣẹ̀, ati nípa òdodo, ati nípa ìdájọ́ Ọlọrun. |
1.219637 | Ya re ba sena go bona, ba mo raya ba re: "Di tlhano le ditlhapi tse pedi." | Nigbati nwọn si mọ̀, nwọn wipe, Marun, pẹlu ẹja meji. |
1.219332 | Jaanong a ba raya a re: "Ka moo he, ntshetsang Kaisara tse e leng tsa Kaisara le Modimo tse e leng tsa Modimo." | "Ó bá sọ fún wọn pé, "Tí ó bá rí bẹ́ẹ̀, ẹ fi ohun tí ó jẹ́ ti Kesari fún Kesari, kí ẹ sì fi ohun tíí ṣe ti Ọlọrun fún Ọlọrun. |
1.219324 | Gonne go tla nna tlalelo e kgolo mo lefatsheng le petso e e bogale mo morafeng o. | Nitori ipọnju nla yio wà lori ilẹ na ati ibinu nla lori awọn eniyan yii. |
Tswana-Yoruba_Sentence-Pairs Dataset
This dataset contains sentence pairs for African languages along with similarity scores. It can be used for machine translation, sentence alignment, or other natural language processing tasks.
This dataset is based on the NLLBv1 dataset, published on OPUS under an open-source initiative led by META. You can find more information here: OPUS - NLLB-v1
Metadata
- File Name: Tswana-Yoruba_Sentence-Pairs
- Number of Rows: 213028
- Number of Columns: 3
- Columns: score, Tswana, Yoruba
Dataset Description
The dataset contains sentence pairs in African languages with an associated similarity score. Each row consists of three columns:
score: The similarity score between the two sentences (range from 0 to 1).Tswana: The first sentence in the pair (language 1).Yoruba: The second sentence in the pair (language 2).
This dataset is intended for use in training and evaluating machine learning models for tasks like translation, sentence similarity, and cross-lingual transfer learning.
References
Below are papers related to how the data was collected and used in various multilingual and cross-lingual applications:
[1] Holger Schwenk and Matthijs Douze, Learning Joint Multilingual Sentence Representations with Neural Machine Translation, ACL workshop on Representation Learning for NLP, 2017
[2] Holger Schwenk and Xian Li, A Corpus for Multilingual Document Classification in Eight Languages, LREC, pages 3548-3551, 2018.
[3] Holger Schwenk, Filtering and Mining Parallel Data in a Joint Multilingual Space ACL, July 2018
[4] Alexis Conneau, Guillaume Lample, Ruty Rinott, Adina Williams, Samuel R. Bowman, Holger Schwenk and Veselin Stoyanov, XNLI: Cross-lingual Sentence Understanding through Inference, EMNLP, 2018.
[5] Mikel Artetxe and Holger Schwenk, Margin-based Parallel Corpus Mining with Multilingual Sentence Embeddings arXiv, Nov 3 2018.
[6] Mikel Artetxe and Holger Schwenk, Massively Multilingual Sentence Embeddings for Zero-Shot Cross-Lingual Transfer and Beyond arXiv, Dec 26 2018.
[7] Holger Schwenk, Vishrav Chaudhary, Shuo Sun, Hongyu Gong and Paco Guzman, WikiMatrix: Mining 135M Parallel Sentences in 1620 Language Pairs from Wikipedia arXiv, July 11 2019.
[8] Holger Schwenk, Guillaume Wenzek, Sergey Edunov, Edouard Grave and Armand Joulin CCMatrix: Mining Billions of High-Quality Parallel Sentences on the WEB
[9] Paul-Ambroise Duquenne, Hongyu Gong, Holger Schwenk, Multimodal and Multilingual Embeddings for Large-Scale Speech Mining, NeurIPS 2021, pages 15748-15761.
[10] Kevin Heffernan, Onur Celebi, and Holger Schwenk, Bitext Mining Using Distilled Sentence Representations for Low-Resource Languages
- Downloads last month
- 8