id int64 0 48 | text stringlengths 103 3.71k |
|---|---|
0 | copyright © 2018 bbc. bbc kò mọ̀ nípa àwọn ohun tí ó wà ní àwọn ojú òpó tí ó wà ní ìta. ọwọ́ tí a fi mú ìbáṣepọ̀ ti ìta. |
1 | ìforúkọsílẹ̀ àwọn olùdìbò àti gbígba káàdì ṣe pàtàkì fún ìlànà ìdìbò bẹ́ẹ̀ sì ni ó ní ipa tí ó ń kó nínú ìsèjọba àwa ara wa, ó ma ń músẹ́ yá nínú ìlànà ìdìbò àti ìsèjọba àwa ara wa. |
2 | àwọn yorùbá ní ọ̀nà tí wọn ń gbà ṣe ìsirọ̀, bẹ́ẹ̀ ní àti ọmọkékeré ní àwọn yorùbá ti ń kọ́ ọmọ wọn ni ìṣirò ní ṣíṣe. wọn yóò ni kí ó máa fi ení, èjì kọrin, ṣere bíi |
3 | ààrẹ fún ẹgbẹ́ àwọn ọmọbíbí ìpínlẹ̀ òndó ní fásitì nàá, popoọla morayọ samson sọ fún bbc pe ìjọba ìpínlẹ̀ òndó ṣèlérí ètò ẹ̀kọ́ ọ̀fẹ́ fún àwọn akẹ́kọ̀ọ́ nàá láti fi tùwọ́n l'ójú. ṣùgbọ́n, ó ní àwọn kò fẹ́ ètò ẹ̀kọ́ ọ̀fẹ́ nàá, ẹ̀dínwó owó ilé-ìwé l'àwọ́n fẹ́. |
4 | níwọ̀ngbà ọjọ́ diẹ tókù kétò ìdìbò sípò gómìnà wáyé nípínlẹ̀ èkìtì, ó ti lé lọ́gọ̀rún àwọn ẹgbẹ́ òkùnkùn tíwọ́n ti mú lọ́kanòjọ̀kan ibùdó tó ń bẹ yíká àwọn ìlú àtabúlé nípínlẹ̀ náà. ọ̀gbẹ́ni hammed sàlàyé pé, gbogbo àwọn ami dúdú kọ̀ọ̀kan tó wà láwọn ìlú àtàwọn abúlé yíká ìpínlẹ̀ náà láwọn tí sèpalẹ̀mọ́ wọn nípasẹ̀ ìfọ... |
5 | ara àwọn nǹkan tí ó sokùn fa ogun àgbáyé àkọ́kọ́ nìyí ogun àgbáyé àkọ́kọ́ yìí bẹ̀rẹ̀ láàárin orílẹ̀-èdè méjì kan tí orúkọ wọn ń jẹ́ austria-humgary ati serbia. ìlú kékeré kan ní awọn orílẹ̀-èdè méjèèjì yìí ń jà lé lórí. orílẹ̀-èdè àkọ́kọ́ ló kọ́kọ́ gba ìlú yìí lọ́wọ́ ẹ̀kẹjì nínú ogun kan tó wáyé ní ọdún 1908. orílẹ̀-èd... |
6 | lọ́wọ́lọ́wọ́ kò sí ìkọ̀ nínú ojúewé yìí. ẹ le wá àkọlé ojúewé yìí nínú àwọn ojúewé mìíràn, tàbí wá àwọn àkọọ́lẹ̀ tó bámu, sùgbọ́n ẹ kò ní àṣẹ láti ṣ'ẹ̀dá ojúewé yìí. |
7 | ẹ̀ka yìí wà fún àwọn àgbájọ, ibi, ilé-iṣẹ́ tàbí àwọn ohun míràn tí wọn jẹ́ dídásílẹ̀ tàbí filọ́lẹ̀ ní ọ̀rúndún 14k. |
8 | ẹgbẹ́ òṣèlú pdp ní gbogbo ariwo ìwé orúkọ àwọn tó jí owó ìlú tí ìjọba orílẹ̀èdè nàíjíríà ń pa báyí kò yẹ̀ lẹ́yín ìgbésẹ̀ láti gbé ojú àwọn ọmọ orílẹ̀èdè nàíjíríà àti àjọ àgbáyé kúrò lóríi ìkùnà ìṣèjọba rẹ̀. |
9 | ẹ̀tẹ̀ ti ń ran àwọn ènìyàn fún àwọn ẹgbẹ̀rún ọdún sẹ́yìn.[3] àrùn yí gba orúkọ rẹ láti látínì ọ̀rọ̀ lepra, tí ó túnmọ̀ sí "scaly", nígbà tí ọ̀rọ̀ "àrùn hansen" wá láti orúkọ oníṣègùn gerhard armauer hansen.[3] yíya àwọn èniyàn sọ́tọ̀ ní awọn ìletò adẹ́tẹ̀ ṣsì ń wáyé ní àwọn orílẹ̀-èdè bíi índíánì, pẹ̀lú iye ju ẹgbẹ̀gbẹ... |
10 | ẹ̀wẹ̀, ìjọba àpapọ̀ orílẹ̀èdè nàìjíríà ti fi àìdunú hàn sí bí wọ́n se ńpa àwọn ọmọ orílẹ̀èdè yìí ní ìlú òyìnbó láì jìnà síra. |
11 | ọ̀jọ̀gbọ́n àti onímọ̀ tó yanrantí ni wọ́n, ní ìgbà ayé e wọn. kò sí akẹ́kọ́ tí kìí sọ ọ̀rọ̀ wọn ní rere. |
12 | àwọn adigunjalè náà pa ọlọ́pàá mẹ́fà àti àwọn ará ìlú mẹ́fà níbi ìkọlù sí àwọn ilé ìfowópamọ́ márùń ní ìlú ọ̀ffà. |
13 | àwọn àdéhùn wọ̀nyí ("àwọn àdéhùn") bo ìlò àwọn àgbéjáde aṣàmúlò microsoft, ojúlé wẹ́ẹ̀bù àti àwọn ìpèsè tí a ṣàkójọ níbí (àwọn "ìpèsè náà"). o gba àwọn ìpèsè wọ̀nyí nípa ṣíṣẹ̀dá àkọọ́lẹ̀ microsoft kan, nípa ìlò rẹ ti àwọn ìpèsè náà, tàbí nípa ìtẹ̀síwájú lati máa lo àwọn ìpèsè náà lẹ́yìn tí a ti sọ àyípadà sí àwọn àdéhù... |
14 | redirect {{àwọn orílẹ̀-èdè áfríkà}} {{àwọn orílẹ̀-èdè ásíà}} {{àwọn orílẹ̀-èdè europe}} {{àwọn orílẹ̀-èdè àríwá amẹ́ríkà}} {{àwọn orílẹ̀-èdè oṣéáníà}} {{àwọn orílẹ̀-èdè gúúsù amẹ́ríkà}} |
15 | ní agbègbè orí òkè nuba ní orílẹ̣̀ èdè sudan ni àwọn ènìyàn tí ó n sọ èdè yìí wọ́pọ̀ sí jùlọ bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ogun àti ọ̀tẹ̀ ti fọ́n ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ènìyàn yìí ká. àtẹ ìṣàlẹ̀ yìí ni ó ṣe àkójọpọ̀ àwọn ìsọ̀rí èdè tí ó wà ní abẹ́ ori èdè kordofanian. |
16 | alukoro iléeṣẹ́ ọlọ́pàá ní ìpínlẹ̀ èkó, tó fìdí ìsẹ̀lẹ̀ náà múlẹ̀ ní, wọn kò tíì mọ ẹnití ọkùnrin naa jẹ́ àti ibití ó ń gbé, bẹ́ẹ̀ ni wọn kò rí ojú ọgbẹ́ ní ara òkú náà. |
17 | nísàlẹ̀ ni àtòjọ àwọn àjápọ̀ mọ́ àwọn ibiìtakùn míràn tí wọ́n únta ìwé tuntun àti ìwé àtijọ́, wọ́n sì le ní ọ̀rọ̀ ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ nípa àwọn ìwé tí ẹ únwá: |
18 | àwọ́n ènìyàn, máa ń rin ìrìnàjò afẹ́ lọ sí ìlú yìí. wọ́n máa ń kan ọkọ̀ ojú omi ńlá níbẹ̀. wọ́n ní àwọn èso wọ́n sì ní àwọn ilé-iṣẹ́ tí ó ń sọ epo dọ̀tun. |
19 | ẹgbẹ́ òsèlú sdp ní ìpínlẹ̀ èkìtì ti ń gbàlèjò ọ̀gọ̀ọ̀rọ̀ ọmọ ẹgbẹ́ òsèlú pdp tó ń ya wá sínú ẹgbẹ́ náà báyìí. |
20 | ológun ojú omi fún àwọn ìpínlẹ̀ aṣọ̀kan amẹ́ríkà jẹ́ ẹ̀ka iṣẹ́ ogun tí ojú omi fún àwọn ìpínlẹ̀ aṣọ̀kan amẹ́ríkà àti pé ó jẹ́ ìkan nínú meje aláṣọ ogun fún àwọn ìpínlẹ̀ aṣọ̀kan amẹ́ríkà. ológun ojú omi fún àwọn ìpínlẹ̀ aṣọ̀kan amẹ́ríkà jẹ́ èyí tọ tọbi jù tí ó sì pójuwọ̀n jùlọ ní gbogbo àgbáyé[1][2][3] tí ó sì ní ohun ì... |
21 | iléesẹ́ ọlọ́pàá ìpínlẹ̀ ògùn ti fìdí rẹ̀ múlẹ̀ pé ọwọ́ òun ti tẹ afurasí mọ́kàndínlọ́gbọ̀n lórí ìpànìyàn tó wáyé ní ìjẹ̀bú igbó ní aago márùń ààbọ̀ ìrọ̀lẹ́ ọ́jọ́ àìkú ní agbègbè òkè-sopen, tó sì sún wọ ìdàjí ọjọ́ ajé, èyí tó tún tàn wọ àwọn àdúgbò míì bíi òkè àgbò àti ojowo. |
22 | nínú ètò ìkànìyàn 1995, àwọn tí ó ń gbé andorra jẹ́ ẹgbẹ̀rún méjì-dún-láàádọrin (68,000). àwọn èdè tí ó jẹ́ ti ìjọba níbẹ̀ ni kàtáláànù tí ìpín ọgọ́ta nínú ọgọ́rùn-ún ń sọ (60%) àti èdè faransé. wọ́n tún ń sọ kàsìtílíànù ti àwọn pànyán-àn-àn gan-an fún òwò àgbáyé àti láti fi bá àwọn tí ó bá wá yẹ ìlú wọn wo sọ̀rọ̀ . |
23 | ìṣàìtó àwọn enzymes àti àwọn ọlọ́kọ̀ tí ó ní ṣe pẹ̀lú ìyípo urea lè fa àwọn àìsàn tí ó rọ̀ mọ́ ìyípo urea bíi: |
24 | ìfihàn àwọn àtúnṣe tí wọn jẹ́ àtúnyẹ̀wò àìpẹ́ nìkan ìfihàn àwọn àtúnṣe tí wọn jẹ́ ìdá ojúewé nìkan fi àwọn àtúṣe kékeré pamọ́ |
25 | ìlù àgẹ̀rẹ̀ jẹ́ ìlù àtijọ́, ìlù àtayébáyé. nítorí ìró aminlẹ̀ tí ó ní, ìlù àgẹ̀rẹ̀ ni ìlù àwọn ògbójú ọdẹ àtijọ́. bákannáà, wọ́n máa ńlù ìlù àgẹ̀rẹ̀ nígbàtí ọlóde tàbí onífa tàbí ọba ìlú bá pa ipò dà. ní àfikún, wọ́n tún máa ńlu ìlù àgẹ̀rẹ̀ fún àwọn ọba àti ìjòyè láti yẹ́ wọn sí. |
26 | owóorí sísan ni ilẹ̀ nigeria wà ni ìbámu pẹ̀lú ìlànà bi wọn se ń se káàkiri àgbáyé. étò yìí ni ó fi àǹfààní sílẹ̀ fun ìdàgbàsòkè, nibi ti àwọn tó ń gba owó osù gọbọi yóò san owóorí wọn gẹ́gẹ́ bí owo tí wọn ń gbà ni gbogbo àkókò supgbọ́n tó jẹ́ wí pé ọ̀pọ̀ àwọn onísẹ́ àdáni, àwọn akọ́sẹ́mọsẹ́ ati àwọn ilé isẹ́ ọlọ́kan-ò... |
27 | ogun ẹkú dédé àsìkò yìí ẹ̀yin ọmọ ogun. ẹ jọ̀wọ́ ẹ jẹ́kí á tún bọ̀ sọwọ́pọ̀ láti gbé ògo ilẹ̀ yorùbá ga.inù mi dùn púpọ̀ sí àwọn ọ̀jọ̀gbọ́n ẹ̀ẹ̀tí kẹ́kọ̀ọ́ tí wọ́n sì jẹ́ ọmọ ilẹ̀ yorùbá yálà nílẹ̀ yorùbá tàbí ní òkè òkun bá lè bẹ̀rẹ̀ láti máa kọ́ ọ̀pọlọ̀pọ̀ nínú àwọn àròkọ wọn ní èdè abínibí wà nítorí òní kọ́ àmọ́ nít... |
28 | ìyá àgbà ó gbẹ́yìn nínú àjọọṣepọ̀ láti kọ́ áwọn ọmọ-ọmọ rẹ̀. èròǹgbà wọn ni láti ríi wípé àjàyi àti àwọn ọmọdé ìyókùn ńhu ìwà ọmọlúàbí. |
29 | ìlù dùndún jẹ́ ọ̀kan pàtàkì nínú àwọn ìlù tí a mọ̀ jùlọ ní ilẹ̀ yorùbá. a le lo ìlù dùndún lóhun nìkan tàbí pẹ̀lú àwọn ìlù míràn láti mú kí ìró ìlù lárinrin létí. ní ayé àtijọ́, àwọn onílù dùndún máa ńfi ìlù yǐ ki àwọn ọba àti àwọn ìjòyè ìlú lójoojúmọ́. fífi ìlù ki àwọn ọba àti àwọn ìjòyè sì wà ní ilẹ̀ yorùbá lónǐ. àw... |
30 | ìwé àjàyí gbọ́ ìtumọ̀ ìlù jẹ́ ìwé tí a ṣe ní ìbámu pẹ̀lú ìmọ̀ ẹ̀rọ òde òní fún àkàgbádùn àwọn ọmọdé pẹ̀lú àwọn òbí. ìwé yǐ fi ìlò èdè àti ẹwà èdè yorùbá bíi òwe, àṣàyàn ọ̀rọ̀, oríkì àti ìjìlẹ̀ ọ̀rọ̀ hàn. bákannáà, ìwé yǐ tún fi àṣà àti ìṣe yorùbá hàn ní ọ̀nà tí ó le rọrùn fún àwọn ọmọdé wa láti tẹ̀lé. |
31 | èròǹgbà làti kọ ìwé yǐ bẹ̀rẹ̀ ní bíi ọdún mélǒ sẹ́yìn nígbàtí ọmọ òǹkọ̀wé yǐ bẹ̀rẹ̀ síí ka àwọn ìwé ọmọdé tí a kọ ní èdè òyìnbo. kò sí irú àwọn ìwé báyǐ ni èdè yorùbá, pàá-pàá jùlọ ní òkè àríwá america. |
32 | àjàyí fẹ́ràn àwọn ẹbí rẹ̀, pàá-pàá jùlọ ìyá àgbà fún ààlọ́ tí wọn máa ńpa nípa ìjàpá ọlọ́gbọ́n ẹ̀wẹ́. àjàyi bá àwọn òbi rẹ̀ lọ sí ibi ìwúyè ní ìlú ayépé, ní ibi tí ó ti pàdé àwọn ọmọ ẹ́gbọ́n ìyá rẹ̀, àdùkẹ́ àti àdùní. àyándìran onílù àrà àti àwọn ọmọ ẹgbẹ́ aríjóyọ̀ sọ ìlù sí wọn ní’bàdí, oyin mọmo, oyin àdò ni! |
33 | àkọọ́lẹ̀ ìṣe ìdínà àti ìgbéìdínàkúrò nìyí. àwọn àdìrẹ́ẹ̀sì ip tí wọn jẹ́ dídílọ́nà nífúnra wọn kò sí nínú àtòjọ yìí. ẹ wo àtòjọ ìdínà fún àtòjọ àwọn gbogbo ohun tí a dílọ́nà báyìí. |
34 | nísàlẹ̀ ni àtòjọ àwọn àtúnṣe sí àwọn àbò ojúewé. ẹ wo àtòjọ àwọn ojúewé aláàbò fún àtòjọ àwọn àbò ojúewé ìgbàyí. |
35 | ìkìlọ̀: ibùdó dátà ti jẹ́ títìpàdé fún ìtọ́jú, nípa bẹ́ẹ̀ ẹ kò ní le fi àwọn àtúnṣe yín pamọ́ lásìkò yìí. tí ẹ bá fẹ́ ẹ le fi ìkọ̀rọ̀ náà pamọ́ sínú fáìlì ìkọ̀rọ̀ fún ìgbà míràn. |
36 | ẹ lọ fọ́ọ̀mù ìsàlẹ̀ láti ṣèrùsókè àwọn fáìlì. láti wò tàbí wá àwọn fáìlì àrùsókè tẹ́lẹ̀ ẹ lọ sí àtòjọ àwọn fáìlì àrùsókè, àwọn à(tùn)rùsókè náà jẹ́ kíkọọ́lẹ̀ nínú àkọọ́lẹ̀ ìrùsókè, àwọn ìparẹ́ nínú àkọọ́lẹ̀ ìparẹ́. |
37 | àwọn fáìlì ìsàlẹ̀ wọ̀nyí jẹ́ lílò sùgbọ́n wọn kò sí. àwọn fáìlì láti ibi-àkósí òkèrè le jẹ́ títò síbẹ̀ bótilẹ̀jẹ́pé wọ́n wà. ìrú àwọn àdájú irọ́ báhun yíò jẹ́ fífagi lé lórí. láfikún, àwọn ojúewé tí wọ́n ní fáìlì tí kò sí nínú jẹ́ títòjọ sínú ẹ̀ka:àwọn ojúewé pẹ̀lú àwọn ìjápọ̀ fáìlì gígé. |
38 | àwọn ẹ̀ka yìí ní ojúewé tàbí amóhùnmáwòrán. àwọn ẹ̀ka aláìlò kò hàn níbí. bákannáà ẹ wo àwọn ẹ̀ka wíwá. |
39 | ilé isẹ́ ọlọ́pàá ní ìpínlẹ̀ náà sọwípé lóòtọ́ ni ìsẹ̀lẹ̀ náà sẹlẹ̀ sùgbọn ènìyàn mẹ́ta làwọn rí òkú rẹ́ nígbà tí àwọn dé ibi ìsẹ̀lẹ̀ náà. tí a kò bá gbàgbé, ìsẹ̀lẹ̀ yíí wáyé lẹ́yìn ọjọ́ díẹ̀ tí àarẹ muhamadu buhari se àbẹ̀wò sí ágbèègbè náà, tó sì se ìpàdé pẹ̀lú àwọn ọba àti àwọn àgbààgbà pẹ̀lú àsẹ wípé kí wọ́n palẹ̀ à... |
40 | kànsí àwọn alaṣẹ apá ilé ayé tí ó jẹ́ ibùgbé ohun ẹlẹmí tí a fi pamọ́ ní orílẹ̀ èdè rẹ kí o sì sọ fún wọn nípa ìdíje yìí ̣ṣe ìfilọ̀ ìdíje yìí pẹ̀lú àwọn ẹgbẹ́ oní fọ́tò, ilé ẹ̀kọ́ gíga àti àwọn ẹgbẹ́ tí ó bá mọ̀ pé ó lè fẹ́ kópa. ìdíje yìí máa jé àànfàní ńlá fún àwọn àwùjọ àti àwọn àjèjì sí awọn apá ilé ayé tí ó jẹ́ ib... |
41 | iléeṣẹ́ ọlọ́pàá ti sọ pé àwọn kò tíì leè sọ bóyá àdó olóró ló bú nílééṣẹ́ ìtoògùn kan ní ìlú ilé ifẹ̀. ọ̀gá ọlọ́pàá nípínlẹ̀ ọ̀ṣun sọ pé irúfẹ́ ìṣẹ̀lẹ̀ náà kò wáyé rí, àwọn yóò sì gbé ìgbésẹ̀ láti dẹ́kun àtúnṣẹ̀ rẹ̀. nígbà tí kọmíṣọ́nà ọlọ́pàá, ọláfimíhàn adéoyè bẹ ibi tí ìṣẹ̀lẹ̀ ìbúgbàmù náà ti ṣẹ̀lẹ̀ wò lọ́jọ́ ajé, ó... |
42 | àwọn agbébọn náà tó máàrún níye nígbà tí wọ́n kọ̀lú àgọ́ ọlọ́pàá náà ní agogo méjì òru ọjọ́ ìṣẹ́gun tí wọ́n sì ṣíná ìbọn bolẹ̀. kòsí ẹni tó lè sọ ní pàtó ohun tó ṣokùnfà ìṣẹ̀lẹ̀ yìí ṣùgbọ́n ìròyìn sọ pé àwọn agbébọn náà gbe ìbọn kan lọ pẹ̀lú àwọn ọta ìbọn. |
43 | wikipedia jẹ́ ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́ tó wà nítorí akitiyan awọn oníse rẹ̀. gbogbo àwọn tí wọ́n kópa nínú iṣẹ́-ọwọ́ yìí lè dá àyọkà tuntun tàbí ṣàtúnṣe àwọn àyọkà tó wà. àfikún kọ̀ọ̀kan únjẹ́ kíkọ sílẹ̀ sínú ìtàn àwọn ojúewé bẹ́ẹ̀sìni wọ́n únhàn nínú àwọn àtúnṣe tuntun. àwọn ohun tí wọn kò bá ní ìbámu pọ̀ mọ́ ìwé ìmọ̀ wikipedia... |
44 | gẹ́gẹ́ bí àwọn ọlọpaa hisbah ṣe sọ, oní nààbì ní àwọn ọmọbinrin yìí, tí wọn sì ń wa àwọn oníbara nínú iṣẹ́ wọn, sùgbọ́n ọ̀pọ̀ àwọn ọmọbinrin yìí ló sọ pe, ìdíkan tàbí òmíràn ló gbé àwọn jáde kúrò nílé ní àsìkò ti wọn mú àwọn. |
45 | ìpínlẹ̀ ẹdó jẹ́ ìkan nínú àwọn ìpínlẹ̀ mẹ́rìndínlógójì ní orílẹ̀ èdè nàìjíríà. ó sàgbè pẹ̀lú àríwá àti ìwọ̀ oòrùn ìpínlẹ̀ kogi, àgbè pẹ̀lú gúúsù ìpínlẹ̀ delta àti ìlà-oòrùn ìpínlẹ̀ ondo. |
46 | àọn àgùdà jẹ́ oníṣòwò pẹ̀lú àwọn benin nígbàyẹn gẹ́gẹ́ bí wọ́n ti ṣàpèjúwe rẹ̀, ó jẹ́ àpẹrẹ́ àjọṣepọ̀ láàrin omi àti ilẹ̀.[17] |
47 | anguidae jẹ́ orúkọ àwọn ẹbí tí ó tóbi tí ó jẹ́ ti aláǹgbá ti northern hemisphere. àwọn tí ó wà ní ẹgbẹ́ yìí ni àwọn slowworm, alángbá gílásì àti alángbá inú omi, àti bẹ́ẹ̀bẹ́ẹ̀ lọ. wọ́n pín ẹbí yìí sí àwọn ẹbí mẹ́ta tí ó sì ní àwọn ẹ̀yà mẹ́rìnlé làádọ́rún ní àwọn ìdílé mẹjọ. wọ́n ní àwọn osteodem tó le ní abẹ́ awọ ara ... |
48 | àwọn olórí ẹgbẹ́ òsìsẹ́ ti sọfún ìjọba àpapọ̀ pe ko fíì ọ̀rọ̀ owó osù tuntun tí wọ́n fẹ́ ma san fún àwọn òsìsẹ́ falẹ̀, bí kòbá fẹ́ kí àwọn òsìsẹ́ fárígá. |
README.md exists but content is empty.
- Downloads last month
- 13