Dataset Viewer
Auto-converted to Parquet Duplicate
audio
audio
transcription
string
Jọ̀ọ́, dòmi
Mo ní ko kawé
Ẹ̀ ti jẹun
Wọ́n ṣiṣẹ́ gidigidi
Ó máa ń jẹun ní òwúrọ̀.
Awon iwé yẹn
ìtàn
Ó ń sùn nígbà tí mo de
Èló ni bàtà naa?
Ó yẹ kẹ yára lọ
Óun ni
Oun kọ́ ni olùkó
gẹ́gẹ́ bó ti wù ú
A máa ṣiṣẹ́ lọ́la
Ilé rẹ
Mo máa ń rerin nigbagbogbo
bóyá
àti
Ilé ńlá
Mo fẹ́ kòkò sinmi
Ó ra kẹ̀kẹ́ látí máa gùn lọ sí ilé ẹ̀kọ́
Wọ́n ti lọ
O ò jẹ́ akẹ́kọ̀ọ́
Kí wọ́n tó bẹ̀rẹ̀
Wọ́n jẹun
Àwa ni
A ò jẹ́ oníṣòwò
Mo fẹ́ lọ sí ilé eko
òru
bàtà
Mà jẹun!
A duro títí di òwúrọ̀
Ṣé o mọ̀ bí a ṣe...?
pàdé
jínnà sí
legbee
Kò sí níbẹ̀
To bá ti dáhùn, m ba ti mọ nkan to fẹ́
Obìnrin kùkùrù
Ẹ̀ ò ní ta a
David bí mí bóyá mo ní owó
Àgọ́ mẹ́ta ni
ṣùgbọ́n
Eyin lo jẹ́ ẹ
Ó yẹ kí n lọ sí ilé ìwòsàn
Tó bá ti rá oyin, a ba ti fi sí ounje wa
Èmi ni
Mo ṣiṣẹ́ kí n lè ṣàṣeyọrí
Báwo ni?
Kí n tó jẹun
Ó ń wá gẹ́gẹ́ bó ti wù ú
Mo ti de
Ó n bẹ̀rù
Èwo lo fẹ́?
Tó bá ti ràn mí lọ́wọ́, m ba ti parí bayìí
Wọ́n ò ti jẹun
Wọ́n ní ka máa bọ̀
Ẹ kúrọ̀lẹ́
Àwa la sare
Iru mọtọ̀ wo ló ní?
David máa ń lo si London ni ọ̀sẹ̀ kookan
Ẹ̀ ò ti sètán
Wọ́n ò ti sètán
Àpò naa
mẹje
ìfẹ̀kúfẹ̀
Ó yẹ ko mu omi púpọ̀
lẹ̀yìn
mu
O ò ti jẹun
Àwọn ni
se
Ta bá lọ, a ò ní pẹ̀ padà
Ó rò pé a kò ní lọ síbi yẹn.
Ta bá ti ṣiṣẹ́, a ba ti gba owó
A n jẹun
Mo maa wa
Wọ́n ò rẹ́rìn
A ò jẹun
O kì í jẹ iresi
Mo máa ń lọ sí ilé ẹ̀kọ́ lẹ́ẹ̀kọ̀ọ̀kan
À kì í ṣe oníṣòwò
Ọkùnrin tó n ṣiṣẹ́
Tẹ bá ti fi tọ́kàntọ́kàn ṣiṣẹ́, ẹ̀ ba ti ṣiṣẹ́ pẹ̀lú wa bayìí
Ẹ̀yin
Tí wọ́n bá ti ṣiṣẹ́, wọ́n bá ti gba owó
James fẹ́ ki n má lọ
Mo gbọ́dọ̀
gbígbóná
Nígbà naa, ó ń jẹun
títí di
Mo maa lọ
Mo ní láti
Ti David bá ti yára, o ba ti wà lọjà bayìí
Tó bá ti dé, a ò ba ni ronu
Ó yẹ ko kòkò jẹun
Ó gbà pé a kò ní lọ síbi yẹn.
tóbi
End of preview. Expand in Data Studio

Yoruba TTS Dataset

A text-to-speech dataset for the Yoruba language.

Usage

from datasets import load_dataset

dataset = load_dataset("oademuwagun/tts-yor")

Dataset Structure

├── metadata.csv
└── wavs/
    ├── yorubatts_00000.wav
    ├── yorubatts_00001.wav
    └── ...

Metadata Format

Column Description
file_name Path to audio file (e.g., wavs/yorubatts_00000.wav)
transcription Yoruba text transcription with proper diacritics

Yoruba Diacritics

The transcriptions include proper Yoruba diacritical marks:

  • Tone marks: acute (́) for high tone, grave (̀) for low tone
  • Underdots: ẹ, ọ, ṣ

License

CC-BY-4.0

Downloads last month
69