audio audio | transcription string |
|---|---|
Jọ̀ọ́, dòmi | |
Mo ní ko kawé | |
Ẹ̀ ti jẹun | |
Wọ́n ṣiṣẹ́ gidigidi | |
Ó máa ń jẹun ní òwúrọ̀. | |
Awon iwé yẹn | |
ìtàn | |
Ó ń sùn nígbà tí mo de | |
Èló ni bàtà naa? | |
Ó yẹ kẹ yára lọ | |
Óun ni | |
Oun kọ́ ni olùkó | |
gẹ́gẹ́ bó ti wù ú | |
A máa ṣiṣẹ́ lọ́la | |
Ilé rẹ | |
Mo máa ń rerin nigbagbogbo | |
bóyá | |
àti | |
Ilé ńlá | |
Mo fẹ́ kòkò sinmi | |
Ó ra kẹ̀kẹ́ látí máa gùn lọ sí ilé ẹ̀kọ́ | |
Wọ́n ti lọ | |
O ò jẹ́ akẹ́kọ̀ọ́ | |
Kí wọ́n tó bẹ̀rẹ̀ | |
Wọ́n jẹun | |
Àwa ni | |
A ò jẹ́ oníṣòwò | |
Mo fẹ́ lọ sí ilé eko | |
òru | |
bàtà | |
Mà jẹun! | |
A duro títí di òwúrọ̀ | |
Ṣé o mọ̀ bí a ṣe...? | |
pàdé | |
jínnà sí | |
legbee | |
Kò sí níbẹ̀ | |
To bá ti dáhùn, m ba ti mọ nkan to fẹ́ | |
Obìnrin kùkùrù | |
Ẹ̀ ò ní ta a | |
David bí mí bóyá mo ní owó | |
Àgọ́ mẹ́ta ni | |
ṣùgbọ́n | |
Eyin lo jẹ́ ẹ | |
Ó yẹ kí n lọ sí ilé ìwòsàn | |
Tó bá ti rá oyin, a ba ti fi sí ounje wa | |
Èmi ni | |
Mo ṣiṣẹ́ kí n lè ṣàṣeyọrí | |
Báwo ni? | |
Kí n tó jẹun | |
Ó ń wá gẹ́gẹ́ bó ti wù ú | |
Mo ti de | |
Ó n bẹ̀rù | |
Èwo lo fẹ́? | |
Tó bá ti ràn mí lọ́wọ́, m ba ti parí bayìí | |
Wọ́n ò ti jẹun | |
Wọ́n ní ka máa bọ̀ | |
Ẹ kúrọ̀lẹ́ | |
Àwa la sare | |
Iru mọtọ̀ wo ló ní? | |
David máa ń lo si London ni ọ̀sẹ̀ kookan | |
Ẹ̀ ò ti sètán | |
Wọ́n ò ti sètán | |
tà | |
Àpò naa | |
mẹje | |
ìfẹ̀kúfẹ̀ | |
Ó yẹ ko mu omi púpọ̀ | |
lẹ̀yìn | |
mu | |
O ò ti jẹun | |
Àwọn ni | |
se | |
Ta bá lọ, a ò ní pẹ̀ padà | |
Ó rò pé a kò ní lọ síbi yẹn. | |
Ta bá ti ṣiṣẹ́, a ba ti gba owó | |
A n jẹun | |
Mo maa wa | |
Wọ́n ò rẹ́rìn | |
A ò jẹun | |
O kì í jẹ iresi | |
Mo máa ń lọ sí ilé ẹ̀kọ́ lẹ́ẹ̀kọ̀ọ̀kan | |
À kì í ṣe oníṣòwò | |
Ọkùnrin tó n ṣiṣẹ́ | |
Tẹ bá ti fi tọ́kàntọ́kàn ṣiṣẹ́, ẹ̀ ba ti ṣiṣẹ́ pẹ̀lú wa bayìí | |
Ẹ̀yin | |
Tí wọ́n bá ti ṣiṣẹ́, wọ́n bá ti gba owó | |
James fẹ́ ki n má lọ | |
Mo gbọ́dọ̀ | |
gbígbóná | |
Nígbà naa, ó ń jẹun | |
títí di | |
Mo maa lọ | |
Mo ní láti | |
Ti David bá ti yára, o ba ti wà lọjà bayìí | |
Tó bá ti dé, a ò ba ni ronu | |
Ó yẹ ko kòkò jẹun | |
Ó gbà pé a kò ní lọ síbi yẹn. | |
bí | |
tóbi |
Subsets and Splits
No community queries yet
The top public SQL queries from the community will appear here once available.