Dataset Viewer
Auto-converted to Parquet Duplicate
S/N
int64
1
436
statement
stringlengths
18
253
A1
stringclasses
2 values
A2
stringclasses
2 values
A3
stringclasses
2 values
target
stringclasses
2 values
source
stringclasses
6 values
text_origin
stringclasses
1 value
1
Lẹ́yìn oúnjẹ, oúnjẹ lókàn. Èmi lókàn!
sarcastic
sarcastic
non-sarcastic
sarcastic
X
original
2
A kò gbọ́dọ̀ purọ́, a kò gbọ́dọ̀ jale, Yorùbá dùn gan!
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
X
original
3
Kò sí bí o bá ṣe ń jìyà tó, má ṣe béèrè ìrànlọ́wọ́ lọ́wọ́ ẹnikẹ́ni. Bó tilẹ̀ jẹ́ pé o lè kú nígbà sórí ìjìyà náà, kò sí ẹni tí yóò lè sọ pé òun ti ràn ọ́ lọ́wọ́ rí
sarcastic
sarcastic
sarcastic
sarcastic
Instagram
original
4
Àsàsí kìí ran baby. Ẹ wí fún aláwo yin tó ní ki ẹ mú orúkọ wá
non-sarcastic
sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
X
original
5
Oṣólẹ̀ Twitter ti gbórí wọlé o, wọ́n ti ń bèèrè wípé kíni orúkọ wà àti orúkọ ìyá tó bí wa lọ́mọ
sarcastic
sarcastic
sarcastic
sarcastic
X
original
6
Tí o bá ṣe ẹ̀ṣẹ̀ kan tí àwọn agbófinró sì ń wá ọ pẹ̀lú ẹ̀bùn tí a gbé lé ọ lórí, lọ kí o sì fi ara rẹ hàn ní àgọ́ ọlọ́pàá. Bó tilẹ̀ jẹ́ pé wọ́n lè fi ọ́ sẹ́wọ̀n, o lè gba ẹ̀bùn náà láti àgọ́ ọlọ́pàá.
sarcastic
sarcastic
sarcastic
sarcastic
Instagram
original
7
Wọ́n ní àwọn kàn fẹ́ lo ọgbọ́n àrékérekè fún wa ni, ni mo ba kí wọn wípé adúpẹ́ tí kò jù báyẹn lọ. Ìyẹn ṣí dára ju jíjàwá lólè lọ
sarcastic
sarcastic
sarcastic
sarcastic
Facebook
original
8
A tọrọ owó lọwọ yín, ẹ sì ní kí a wáa gba nílé, èwo ló wáá fa ẹ̀wọ̀n?
non-sarcastic
sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
Facebook
original
9
Ọmọ náà pupa bíi tááyà ọkọ
sarcastic
sarcastic
sarcastic
sarcastic
Crowdsourcing
original
10
Ìwọ lo gbọ́n jù nínú gbogbo ọmọ tí ìyá rẹ bí, ọlọ́pọlọ ẹja
sarcastic
sarcastic
sarcastic
sarcastic
Crowdsourcing
original
11
Àìgbọ́fá là ń wòkè, ifá kan kòsí ní párá
non-sarcastic
sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
Crowdsourcing
original
12
Ọ fẹ́ẹ́ mọ ibi tó yẹ kí o gbesí àbí? O lè wáá gbe sími lórí
sarcastic
sarcastic
sarcastic
sarcastic
Crowdsourcing
original
13
Kò níí da fún ọmọ ìyá tí kò fẹ́ràn ara wọn
non-sarcastic
sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
Facebook
original
14
Ó bimí léèrè wípé eré wo ni ká wò, mo sì nì kó jẹ́ kí a wo wèrè
sarcastic
sarcastic
sarcastic
sarcastic
Facebook
original
15
Má bẹ̀rù láti wà ní àtìmọ́lé, nítorí o lè pàdé olùrànlọ́wọ́ rẹ níbẹ̀, bó tilẹ̀ jẹ́ pé o máa jìyà nínú ẹ̀wọ̀n.
sarcastic
sarcastic
sarcastic
sarcastic
Instagram
original
16
Oò ṣe kúkú lọ gbé gbogbo ẹrù rẹ kí o ṣí mọ́rí kí o máa bọ̀ nílé ọkọ tèmi?
sarcastic
sarcastic
sarcastic
sarcastic
Facebook
original
17
Tí o bá yá ẹnìkan lowó tí o kò sì mọ ibi tí ó wà mọ́, wá ẹnìkan tí ó sún mọ́ ọn kí o sì tún yá ìyẹn náà lówó, bó tilẹ̀ jẹ́ pé o lè má rí owó méjèèjì gbà
sarcastic
sarcastic
sarcastic
sarcastic
Instagram
original
18
Ọmọ yí gọ̀, ó fi ẹnu ọ ara
non-sarcastic
sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
Crowdsourcing
original
19
Òṣèlú ilẹ̀ Nàìjíríà ló dára jù ní gbogbo àgbáyé!
sarcastic
sarcastic
sarcastic
sarcastic
Crowdsourcing
original
20
A nílo àwọn aṣojú tó kájú òṣùwọ̀n
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
Crowdsourcing
original
21
Ìwúrí ńlá ni fún mi pé ààrẹ ẹgbẹ́ ọmọ Yorùbá ni ìlú Faransé wá si pápákọ̀ òfúrufú láti wá gbé mi loni ni ìlu parisi lai fun wọn asiko tó tó
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
X
original
22
Awakọ̀ kan wa ọkọ̀ wọ ààrin èrò níbi tí wọn tí ń ṣ'àjọ̀dún, ọ̀pọ̀ ẹ̀mí sùn
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
23
Gbogbo ẹ̀ka ọrọ̀ ajé, ètò ìrìnnà, iléèwòsàn, àti àwọn ilé ìtajà ló ti dẹnukọlẹ lẹ́yìn tí iná lọ ní orílẹ̀èdè méjèéjì.
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
24
Ṣé lóòtọ́ ni Gómìnà Adeleke ń gbèrò láti bẹ́ kìjà kúrò ní PDP lọ sí APC?
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
25
Ṣé lóòótọ́ ni pé Naijiria ti di orílẹ̀èdè ẹlẹ́gbẹ́ òṣèlú kan?
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
26
Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
27
"Wọ́n fẹ́ pààyàn ni" - BBC ṣe ìdánimọ̀ àwọn ẹ̀ṣọ́ aláàbò tó yìnbọn p'àwọn tó ṣèwọ́de tako owó orí tuntun ní Kenya
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
28
Lẹ́yìn ìsìnkú Póòpù Francis, Ìjọ Kátólíìkì kéde ọjọ́ tí wọn yóò yàn póòpù tuntun
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
29
NDIC bẹ̀rẹ̀ sísan owó fún àwọn tó fowópamọ́ sí Heritage Bank to kógbáwọlé
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
30
Ẹsẹ̀ ẹlẹ́sẹ̀ níí gbé òkú wọ isà
non-sarcastic
sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
YouTube
original
31
FBI mú èèyàn 22 ní Naijiria fún ẹ̀sùn fífi àwòràn ìhòhò lu jìbìtì lórí ayélujára
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
32
Àjọ NAPTIP dóòlà ọmọ Naijiria mẹ́sàn-an tí wọ́n fẹ́ẹ́ tàn ṣòwò ẹrú lọ si Libya
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
33
Ìbúgbàmù Iran gbẹ̀mí èèyàn méjìdínlógún, 800 míì farapa
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
34
Oyinkan Abayomi: Ajàfẹ́tọ̀ọ́ ẹni tó dá ẹgbẹ́ òṣèlú obìnrin àkọ́kọ́ sílẹ̀, tó tún jà fún ètò ẹ̀kọ́, ìṣèlú àti òmìnira obìnrin
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
35
Bí ètò ìsìnkú Pope Francis yóò ṣe wáyé àti àwọn èèyàn tí yóò wà níbẹ̀
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
36
NiMET dá ìyanṣẹ́lódì dúró, fún ìjọba ní gbèdéke láti dáhùn àwọn ìbéèrè wọn
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
37
Àwọn òrìṣà méje ìṣẹ̀mbáyé tó di ilẹ̀ gbogbo àgbáyé mú
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
38
Alàgbà ni ọkọ mi ní ṣọ́ọ̀ṣì, wòólì ni mí fún ogún ọdún kí ń tó di Yeye Olokun - Omolara Fanimokun
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
39
Iléeṣẹ́ ológun bẹ̀rẹ̀ ìgbésẹ̀ ọ̀tun lóri ẹgbẹ́ agbébọn Mahmuda tó n ṣoro ní Kwara
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
40
'Gbèsè ni mo fi tọ́ àwọn ìbejì tó gba First Class, tayọ jù lọ ní UI'
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
41
'A kàn ṣàdédé rí àwọn agbébọn tí wọ́n ṣíná ìbọn bolẹ̀, pa èèyàn mẹ́jọ, inú ìbẹ̀rù là ń gbé báyìí'
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
42
Ẹ fura o! Èèyàn 135,000 ló ní HIV l'Eko nìkan - Wo bí o ṣe lè dáàbò bo ara rẹ
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
43
Báwo ni àwọn ohun èèlò ìkunjú tí ò ń lò ṣe burú sí?
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
44
Ṣé lóòótọ́ ni pé ilé ejọ̀ ní kí wọ́n fi Simon Ekpa ránṣẹ́ sí Naijiria?
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
45
Ọwọ́ ọlọ́pàá tẹ àwọn tó ń fi èèyàn ṣòwò ẹrú ní Ibadan, dóòlà èèyàn 84
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
46
Wọ́n ti sin òkú Pope Francis - Ẹ wo bí ètò ìsìnkú nàá ṣe lọ
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
47
Akọrin tàkasúfèé, Terry Apala, di èèrò ẹ̀wọ̀n fún ẹ̀sùn pé ó tàbùkù owó náírà
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
48
Ó sàn kí o dá ilémoṣú ju kí o máa tẹríba fọ́kùnrin lọ
sarcastic
sarcastic
sarcastic
sarcastic
BBC News
original
49
Wo ànfààní tó wà nínú jíjẹ́un làí kánjú
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
50
Bí o ṣe le lo Etí Erin (Aloe Vera) fún ìṣaralóge àti ìwòsàn àgọ́ ara
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
51
Ǹ jẹ́ ò ń fọ nǹkan ìmumi rẹ dáadáa bó ṣe yẹ?
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
52
Ṣe ó ṣeéṣe kí wọ́n yan Póòpù tuntun láti Africa?
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
53
Láti ìbẹ̀rẹ̀ ni ọkọ mi ti lawọ́ sí mi, lèmi náà gbọdọ̀ ṣe jẹ́ ọmọ dáadáa - Shade Okoya
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
54
'Ebi kọ́ ló mú kí àwọn ọmọ mi máa bá mi ṣiṣẹ́ fọga, kí ọjọ́ ọ̀la wọn le dára ni'
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
55
'Mò n fi èdè Ìjẹ̀bú kọ́ àwọn akẹ́kọ̀ọ́ mi ní ìṣirò nítorí mo fẹ́ kó yé wọn dáàdáà'
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
56
Ìlú Igboho rèé, níbi tí ọba mẹ́ta ti ń ṣèlú, ta ni ojúlówó ọba láàrin wọn?
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
57
Ṣó o láyà? Tope Osoba fakọyọ nínú ìmọ̀ èdè Yoruba
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
58
"N kò bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ ilé kíkùn pẹ̀lú owó gbígbà, owó ọkọ̀ àti oúnjẹ Noodles nìkan ni wọn ń fún mi"
non-sarcastic
sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
59
"Àpá tó so sí àgbọ̀n mi (Keloid) ló fa iṣẹ́ abẹ, mo lọ tan iná sójú ọgbẹ́ náà àmọ́ UCH fọ́ mi lójú"
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
60
Russia rọ̀jò àdó olóró sórí Ukraine, èèyàn 34 kú, 117 míì farapa
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
61
Ohun tó yẹ kí o mọ̀ nípa ẹgbẹ́ agbébọn Mahmuda tó ń ṣoro nípìnlẹ̀ Kwara
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
62
Báwo ni wọ́n ṣe ń yan Póòpù tuntun?
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
63
Pásítọ̀ kó sí gbaga fún ṣíṣe aṣemáṣe pẹ̀lú ọmọdé tó jẹ́ àkàndá l'Ondo
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
64
Afurasí tó ń ṣagolo-ṣàgò gún ọmọ-ọmọ olórin Asiko, Comfort Omoge pa l'Ondo
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
65
Èyí ni ìdí tí mo ṣe fi iṣẹ́ Fada sílẹ̀ nínú ìjọ Àgùda, tí mo sì di oníṣẹ̀ṣe
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
66
Ọmọ Ghana mẹ́sàn án tí wọ́n fi iṣẹ́ tàn kúrò nílé, bá ara wọn nígbèkùn ní Mowe, nípìnlẹ̀ Ogun
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
67
Francis, ẹ̀ṣọ́ aláàbò nílé ijó tó di Póòpù tó mú àyípadà ńlá bá ìjọ Kátólíìkì
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
68
Kìnìún wọ ilé onílé, ó pa ọmọ ọdún mẹ́rìnlá
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
69
Àwọn ajínigbé ṣọṣẹ́ ní Kwara, jí gbogbo èèrò inú ọkọ̀ gbé
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
70
Lo ojú òpó yìí láti mọ̀ bóyá o ní ìfúnpá gíga tàbí wà nínú ewu láti ní i
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
71
Akẹ́kọ̀ọ́ fásitì OAU gan mọ́ iná lásìkò tó ń gbá bọ́ọ̀lù
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
72
Christian Chukwu, akọ́nimọ̀ọ́gbá Super Eagles tẹ́lẹ̀, jáde láyé
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
73
Kí ló dé tí ẹnu fi ń kun ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù 3SC ilẹ̀ Ibadan?
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
74
Ṣé lóòtọ́ọ́ ní pé gbèsè ló lé Segun Olanrewaju, abẹ̀sẹ́kùbíòjò tó kú lójú ìjà, padà sídìí ẹ̀ṣẹ́ kíkàn? Àwọn mọ̀lẹ́bí rẹ̀ sọ̀rọ̀
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
75
Abẹ̀ṣẹ́kú-bí-òjò, George Foreman, jáde láyé
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
76
Bàbá onílé yìnbọn mọ́ ọmọdé tó gbá bọ́ọ̀lù sínú ọgbà ilé rẹ̀, ọ̀rọ̀ bẹ́yìn yọ
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
77
'Ìfẹ́ tí mo ní sí ọ̀bọ ló jẹ́ kí n bẹ̀rẹ̀ eré ìdárayá lílo ọwọ́ àti ẹsẹ̀ fi sáré'
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
78
Karim Adeyemi, agbábọ́ọ̀lù ọmọ Naijiria tó ń ran àwọn ọ̀dọ́ lọ́wọ́
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
79
Mọ̀ nípa ọdún eégún ìlú Ekan-Meje, níbi tó ti jẹ́ èèwọ̀ láti gbé àjẹkù oúnjẹ́ lọ sílé látibi ọdún
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
80
Eniola Badmus àti Laide Bakare fìjà pẹ́ẹta níbi ìfilọ́lẹ̀ fíìmù Eniola Ajao
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
81
Wo iléẹ̀kọ́ àwọn olóyún tí wọn ti ń gba àmì ẹ̀yẹ fún ijó jíjó, oge ṣíṣe àti ìmọ́tótó
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
82
Agbébọn jí pásítọ̀ gbé lásìkò ìwàásù nínú ṣọ́ọ̀ṣì
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
83
Mi ò kábàmọ́ọ̀ pé ìyàwó mi tó kú nigbà tó fẹ́ bímọ kò forúkọ sílẹ̀ nílé ìwòsàn - Folajimi
non-sarcastic
sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
84
Àní ká fi ọ̀rọ̀ ọ̀hún mu tábà ní gbẹ́rẹ́fu. Ọ̀rọ̀ burúkú tòun tẹ̀rín
non-sarcastic
sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
85
Ẹ tún fẹ́ gbé wa mọ́ra àbí? Ẹ ti pawó sápò yín tán àbí bẹ́ẹ̀ kọ́?
non-sarcastic
sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
86
Pàtàkì ni oyè Kudẹfù lóde Ọ̀yọ́, Gẹ́gẹ́bí aláàfin tó bá jẹ, bí èèyàn bá ti jẹ Kúdẹfù kò gbọdọ̀ fi ààfin Ọ̀yọ́ sílẹ̀
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
X
original
87
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ fóònù olówó iyebíye tuntun ló jóná nínú ìjàmbá iná ọ̀hún
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
88
Nlẹ o, abéwúrẹ́ sọ̀rọ̀, wọ́n ti kọ̀ǹgọ́ bọ ìlù
non-sarcastic
sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
89
Ìgbà gbá mi dànù, mo wá ńhùwà bí àkọ́ọ̀gbà
sarcastic
sarcastic
non-sarcastic
sarcastic
YouTube
original
90
Ata gígún ni ilé ayé
sarcastic
sarcastic
non-sarcastic
sarcastic
YouTube
original
91
O ti ní ìríríi táláká púpọ̀
sarcastic
sarcastic
sarcastic
sarcastic
YouTube
original
92
Níbi tí mo ti ń ṣiṣẹ́, bàbá, mo wọ́ ike owó kan ni jàre
sarcastic
sarcastic
non-sarcastic
sarcastic
YouTube
original
93
Kílọdé tí o ní éńjìnì Benz tí o wá ńfi kórópe wàá?
sarcastic
sarcastic
non-sarcastic
sarcastic
YouTube
original
94
Tí wọ́n bá ti nfi ọkọ ayọ́kẹ́lẹ́ gbe ènìyàn, yóò ma yọ́ kẹ́lẹ́kẹ́lẹ́ nọ́ọ̀ni
sarcastic
sarcastic
non-sarcastic
sarcastic
YouTube
original
95
Lẹ́yìn ò rẹyìn, EFCC ṣàlàyé ìdí tí VDM fi wà ní àhámọ́ rẹ̀
sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
YouTube
original
96
Ọọ̀ní ṣe pàtàkì fún ìṣọ̀kan àti ìlọsíwájú Naijiria – Goodluck Jonathan
sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
YouTube
original
97
Ìdí rèé tí Ọlọ́pàá àti Amotekun ṣe kọjú ìjà síra wọn l'Ondo, tí ọ̀pọ̀ èèyàn sì farapa
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
98
Kí ló ń fa àṣìṣe lórí ètò ẹ̀yáwó akẹ́kọ̀ọ́, táwọn akẹ́kọ̀ọ́jáde fi ń rí ẹ̀yáwó náà gba?
non-sarcastic
sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
99
"Amotekun gbé àbúrò mi lọ́jọ́ Àìkú, pa á lọ́jọ́ Ajé, ọ̀gá wọn ń bẹ̀ mi, kí ń gba N1m láti fi sin ín"
non-sarcastic
sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
100
Ìyàwó ilé méjì dèrò ẹ̀wọ̀n fún fífi PoS ta owó náírà tó tó N3.8m àti N1.6m
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
End of preview. Expand in Data Studio

Dataset Card for Yor-Sarc

Yor-Sarc is a gold-standard dataset for sarcasm detection in Yorùbá, a tonal and morphologically rich low-resource African language spoken by over 50 million people. The dataset was created to address the scarcity of high-quality annotated resources for figurative language understanding in African NLP.

It contains 436 manually annotated Yorùbá text instances labeled for binary sarcasm classification.


Dataset Details

Dataset Description

Yor-Sarc aims to accelerate research in Yorùbá NLP and broader low-resource African language modeling by providing a carefully curated benchmark dataset for sarcasm detection.

Unlike coarse-grained sentiment datasets, Yor-Sarc focuses on fine-grained figurative language understanding, specifically sarcasm — a pragmatically complex phenomenon that depends on tone, context, and cultural cues.

Each instance:

  • Is written in Standardized Yorùbá orthography (with diacritics)
  • Is annotated with a binary label such that we could eventually have:
    • 0 = non-sarcastic
    • 1 = sarcastic
  • Was independently labeled by three native Yorùbá speakers
  • Preserves annotator agreement for uncertainty-aware modelling

The dataset achieves substantial inter-annotator agreement:

  • Fleiss’ κ = 0.7660
  • Pairwise Cohen’s κ = 0.6732–0.8743
  • 83.3% unanimous agreement

Yor-Sarc provides a foundational benchmark for evaluating machine learning, deep learning, and large language model (LLM) approaches for sarcasm detection in low-resource settings.


  • Curated by: Toheeb Aduramomi Jimoh, Tabea De Wille, Nikola S. Nikolov
  • Language(s): Yorùbá (yo)
  • License: CC-BY-4.0

Dataset Sources


Uses

Direct Use

Yor-Sarc is intended for research in:

  • Sarcasm detection
  • Figurative language understanding
  • Sentiment and emotion analysis
  • Low-resource NLP
  • African language modelling
  • Cross-lingual transfer learning
  • Uncertainty-aware and disagreement-aware modeling

It is suitable for benchmarking:

  • Machine learning models
  • Deep learning architectures
  • Transformer-based models
  • Large Language Models (LLMs)

Out-of-Scope Use

This dataset should not be used for:

  • Surveillance or profiling

Dataset Structure

Total instances: 436

Each record contains:

  • text: Yorùbá sentence (with diacritics)
  • label: Majority-vote binary sarcasm label
  • (Optional) Annotator vote proportions for soft-label modeling

Agreement distribution:

  • 83.26% unanimous agreement (3–0)
  • 16.74% majority agreement (2–1)

Dataset Creation

Curation Rationale

Sarcasm detection research is heavily dominated by English and other high-resource languages. Yorùbá lacks publicly available gold-standard sarcasm datasets despite its linguistic richness and widespread usage.

Yor-Sarc was created to:

  • Provide a culturally grounded benchmark
  • Support African NLP research
  • Encourage figurative language modeling in tonal languages
  • Enable robust evaluation of sarcasm detection systems in low-resource settings

Source Data

Data were collected from:

  • Yorùbá news platforms
  • Social media platforms (X, Facebook, Instagram, YouTube captions)
  • Crowdsourced contributions

All texts were cleaned and standardized before annotation.


Data Collection and Processing

  • Web scraping, Manual collection and filtering
  • Standardized orthographic normalization
  • Three independent native-speaker annotations
  • Majority voting for final labels
  • Agreement metrics computed using Cohen’s κ and Fleiss’ κ

Annotations

Annotation Process

  • Three native Yorùbá annotators
  • Binary sarcasm labeling
  • Iteratively refined guidelines
  • Independent annotation
  • Statistical agreement validation

Who are the annotators?

Native Yorùbá speakers with linguistic proficiency and familiarity with dialectal variation. Annotators were independent and compensated fairly.


Personal and Sensitive Information

The dataset contains publicly available and voluntarily contributed texts. Personally identifiable information has been removed where necessary. No sensitive metadata is included.


Bias, Risks, and Limitations

  • Relatively small dataset size (436 instances)
  • Non-exhaustive domain coverage
  • Cultural understanding influences sarcasm interpretation

Citation

If you use Yor-Sarc, please cite:

BibTeX:

@misc{jimoh2026yorsarcgoldstandarddatasetsarcasm,
      title={Yor-Sarc: A gold-standard dataset for sarcasm detection in a low-resource African language}, 
      author={Toheeb Aduramomi Jimoh and Tabea De Wille and Nikola S. Nikolov},
      year={2026},
      eprint={2602.18964},
      archivePrefix={arXiv},
      primaryClass={cs.CL},
      url={https://arxiv.org/abs/2602.18964}
}
Downloads last month
8

Paper for toheebadura/yor-sarc