Dataset Viewer
Auto-converted to Parquet Duplicate
audio
audioduration (s)
0.38
572
text
stringlengths
4
5.59k
speaker_id
stringclasses
36 values
age_group
stringclasses
2 values
domain
stringclasses
3 values
gender
stringclasses
2 values
Orílẹ̀-èdè Ghana jẹ́ ibi tó rẹwà
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
Ẹ̀gbẹ́ Ìbàdàn ni Èkó wà.
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
Olú-ìlú ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun ni Òṣogbo
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
Ìrẹ́sì ni oúnjẹ àwọn ọmọdé
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
Ọ̀la ni ọdún iléyá
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
Ọba ìlú Ilé-Ifẹ̀ ni Ọba Adeyeye Ogunwusi.
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
Gómìnà ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ni Ọ̀gbẹ́ni Seyi Makinde
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
Gómìnà ìpínlẹ̀ Èkó ni Ọ̀gbẹ́ni Sanwo Olu
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
Ilé-ìwé gíga Obáfẹ́mi Awólọ́wọ̀ wà ní ìlú Ilé-Ifẹ̀.
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
Dandan ni kí n jẹ Àmàlà l'ójojúmọ́
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
Gómìnà ìpínlẹ̀ Ògùn ni Ọ̀gbẹ́ni Dapo Abiodun.
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
Ọdún Kérésì yìí máa dùn
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
Ìlú Àbújá ni olú-ìlú orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
Ọba ìlú Ilé-Ifẹ̀ ni Ọba Adeyeye Ogunwusi.
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
Àwọn ológun lórí ń darí Malì
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
Agbègbè Ìkòyí ní ìlú Èkó jẹ́ agbègbè tí àwọn olówó wà jù lọ.
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
Nìjẹ̀ẹ́ pa àlà pẹ̀lú Sokoto
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
Olú-ìlú Israeli ni Tel-aviv
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
Fásitì Ìbàdàn ni àkọ́kọ́ ní Nàìjíríà
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
Olú-ìlú Amerika ni Washington DC
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
ọ̀la ni ọjọ́ ìṣẹ́gun
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
Ta ni gómìnà ìpínlẹ̀ Ògùn? Gómìnà ìpínlẹ̀ Ògùn ni Ọ̀gbẹ́ni Dapo Abiodun.
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
Mo ti ra ẹran iléyá
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
Èkuru ni oúnjẹ àwọn ìbeji
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
Òkun Atlantic wà láàárín Amerika àti Afrika
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
Òkè tó ga jù ní àgbáyé ni Òkè Everest ní Fiji
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
Èkìtì ni ó kéré jù ní apá gúúsù ìwọ̀-oòrùn Nàìjíríà
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
Òkè Olúmọ ga púpọ̀, ó wà ní ìpínlẹ̀ Ògùn
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
Ta ni Ọba olórin Jùjú? Ọba orin Sunny Adé
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
Òkè Láyípo ni ibi tó ga jù lọ ní Ìbàdàn
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
Bẹ̀nẹ̀ àti Ṣakí pa àlà pẹ̀lú ara wọn
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
APC ni ẹgbẹ́ òṣèlú tó ń ṣejọba ní Nàìjíríà báyìí
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
Iyán àti ẹgúsí máa ń yo èèyàn dáadáa
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
Ọ̀la ni àwọn INEC máa parí kíkà ìbò
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
Ta ni Ọba ìlú Ilé-Ifẹ̀? Ọba ìlú Ilé-Ifẹ̀ ni Ọba Adeyeye Ogunwusi.
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
Òní ni ọjọ́ ajé,
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
Àpáta ńlá ni Zuma, ọ̀nà Àbújá ló wà
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
Àwọn ọmọ Yorùbá wà ní Kòtọnú
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
Ọ̀túnla ni ọjọ́rú, ọjọ́bọ̀ ni mo máa lọ sí ilé
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
Ilẹ̀ Yorùbá ni Ìlọrin
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
Ìbàdàn àti Abẹ́òkúta pa àlà pẹ̀lú ara wọn.
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
Èkó ni mo ti máa ṣe ọdún òmìnira
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
ọjọ́bọ̀ ni mo máa lọ sí ilé
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
Mo máa jó gidi gan l'ọ́jọ́ ìkóre tó ń bọ̀ yìí
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
Ẹkọ tútù àti àkàrà dára fún oúnjẹ alẹ́
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
Èdè wo ni wọ́n ń sọ ní Bẹ̀nẹ̀?
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
Ògì la máa ń kọ́kọ́ mu l'áàrọ̀
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
Ojojúmọ́ la ń jẹ ìrẹ́sì
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun ni Àṣẹ́jìre wà
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
Wakọ̀ láti Ọ̀gagun sí Ibi Watertower, lọ sí àríwá lórí Park Drive sí East Grand Avenue.
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
Ààrẹ Bola Tinubu ni ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà láti ọdún 2023 títí fi di òní.
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
Ṣé wọ́n ń sọ gẹ̀ẹ́sì ní Kòtọnú?
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
CAF ti wọ́gi lé ètò ìdìbò sí ipò ààrẹ ẹgbẹ́ náà
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
Kòtọnú, Nìjẹ̀ẹ́, Malì
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
Omi gbígbóná àti tútù pàdé ní Ìkogosí
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
Mo ti ra adìẹ láti ṣe ọdún Maoludi
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
Ìrẹ́sì àti ẹ̀wà dára l'ára
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
Ọjọ́ Ẹtì ni ọdún Àjíǹde bọ́ sí
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
Mo ti ra aṣọ fún ọdún eégún
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
Yípadà sí apá òsì sí East Grand kí o tẹ̀síwájú ìbùsọ̀ méjì títí o fi dé ìdàpọ̀ pẹ̀lú Lakeshore Drive.
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
Yípadà sí apá ọ̀tún sí Lakeshore kí o wakọ̀ ìbùsọ̀ 0.3 ṣáájú kí o tó yípadà sí apá òsì sí East Chestnut Street.
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
Mo ń lọ sí ibi àsè ìgbéyàwó l'ọ́jọ́ àbamẹ́ta
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
Láti dé Agbówó láti Àgọ́dì, o máa wọ mọ́tò láti Àgọ́dì dé Bodìjà, o máa rìn fún ìṣẹ́jú márùn-ún.
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
Ìlú wo ni 9ice Alapomeji ti wà? Ìlú Ògbómọ̀ṣọ́ ni 9ice ti wà
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
Ìlú wo ni Àṣẹ́jìre wà? Odò Àṣèjìrẹ́ wà ní ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun, ó pàálà pẹ̀lú Ìbàdàn
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
Àwọn oúnjẹ wo ni a lè rí l'ára ẹ̀wà: a lè rí àkàrà, mọ́ínmọ́ín, èkuru, àti gbẹ̀gìrì l'ára ẹ̀wà
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
Omi pọ̀ ju ilẹ̀ lọ ní Èkó
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
Ìlú wo ni Odò Eléyẹlé wà? Ìlú Ìbàdàn ni Eléyẹlé wà ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
FIFA ti fi òfin de Samson Siasia
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
Àwọn alárìíyá lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà ni Sunny Adé, Ebenezer Obey, Ọlamide Badoo, Wizkid, 9ice Alapomeji àti Davido
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
Ẹnì kọ̀ọ̀kan ló ní ẹ̀tọ́ láti dá ohun ìní ara rẹ̀ ní, tàbí láti ní-in papọ̀ pẹ̀lú àwọn mìíràn. A kò lè ṣàdédé gba ohun ìní ẹnì kan lọ́wọ́ rẹ̀ láìnídìí.
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
Òkun, Zuma, Àṣẹ́jìre, Fásitì Ìbàdàn, Òkè Láyípo, Odò Niger, Ikogosi, Òkè Olúmọ, Odò Eléyẹlé
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
Bí o bá ń lọ sí Yémẹtu láti Òjé, o máa wọ ọkọ̀ láti Òjé fún bí i ìṣẹ́jú márùn-ún, o máa sọ ní ìyànà Adéoyò, rìn sí apá ọ̀tún, o máa rí Yémẹtu lọ́ọ̀kán.
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
Agùgù sí Lágẹlù ò jìnnà rárá, o máa rìn fún ìṣẹ́jú mẹ́wàá, o máa pàdé ìyànà méjì lápá òsì rẹ̀, má ṣe yà, máa lọ títí o máa fi rí ẹnu ìloro Lágẹlù.
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
Ta ni ó ní àmì-ayò tó pọ̀ jù fún Super Eagles? Rashidi Yekini ló ní àmì-ayò tó pọ̀ jù fún orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, ó kú ní ọdún 2014
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
Wọ ọkọ̀ akérò tó ń lọ sí Mọ́kọ́lá láti Àgọ́dì-Gate, sọ ní Mọ́kọ́lá, yà sí apá òsì rẹ, ka ilé méje, ilé keje ni Ìjọ Baptist wà.
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
Ìṣẹ́jú márùn-ún ni o máa fi wakọ̀ láti Benue road dé gbọ̀ngan CBN, máa tọ ìyànà apá ọ̀tún rẹ̀ lọ, o máa débẹ̀ láìpẹ́.
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
Ààrẹ Bola Tinubu ni ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà láti ọdún 2023 títí fi di òní. Ó ti jẹ́ gómìnà ìpínlẹ̀ Èkó láti ọdún 1999 títí di ọdún 2007. Ìyàwó rẹ̀ ni Oluremi Tinubu. Àwọn gómìnà ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ àti Ògùn ni Ọ̀gbẹ́ni Seyi Makinde àti Ọ̀gbẹ́ni Dapo Abiodun. Olú-ìlú ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun ni Òṣogbo. Ọba ìlú Ilé-Ifẹ̀ ni Ọba Adeyeye O...
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
Tọkùnrin tobìnrin tó bá ti bàlágà ló ní ẹ̀tọ́ láti fẹ́ ara wọn, kí wọ́n sì dá ẹbí ti wọn sílẹ̀ láìsí ìkanilápá-kò kankan nípa ẹ̀yà wọn, tàbí orílẹ̀-èdè wọn tàbí ẹ̀sìn wọn. Ẹtọ́ wọn dọ́gba nínú ìgbéyàwó, ìbáà jẹ́ nígbà tí wọ́n wà pọ̀ tàbí lẹ́yìn tí wọ́n bá kọ ara wọn. A kò gbọ́dọ̀ ṣe ìgbéyàwó kan láìjẹ́ pé, àwọn tí ó fẹ...
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
Ẹnì kọ̀ọ̀kan ló ní ẹ̀tọ́ láti ṣiṣẹ́, láti yan irú iṣẹ́ tí ó wù ú, lábẹ́ àdéhùn tí ó tọ́, tí ó sì tún rọrùn, kí ó sì ní ààbò kúrò lọ́wọ́ àìríṣẹ́ ṣe. Ẹnì kọ̀ọ̀kan ló ní ẹ̀tọ́ láti gba iye owó tí ó dọ́gba fún irú iṣẹ́ kan náà, láìsí ìyàsọ́tọ̀ kankan. Ẹnì kọ̀ọ̀kan tí ó bá ń ṣiṣẹ́ ní ẹ̀tọ́ láti gba owó oṣù tí ó tọ́ tí yóò s...
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
A kò gbọ́dọ̀ túmọ̀ ohunkóhun nínú ìkéde yìí gẹ́gẹ́ bí ohun tí ó fún orílẹ̀-èdè kan tàbí àkójọpọ̀ àwọn ènìyàn kan tàbí ẹnikẹ́ni ní ẹ̀tọ́ láti ṣe ohunkóhun tí yóò mú ìparun bá èyíkéyìí nínú àwọn ẹ̀tọ́ àti òmìnira tí a kéde yìí.
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
Ẹnì kọ̀ọ̀kan ló ní ẹ̀tọ́ láti kọ́ ẹ̀kọ́. Ó kéré tán, ẹ̀kọ́ gbọ́dọ̀ jẹ́ ọ̀fẹ́ ní àwọn ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀. Ẹ̀kọ́ ní ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ yìí sì gbọ́dọ̀ jẹ́ dandan. A gbọ́dọ̀ pèsè ẹ̀kọ́ iṣẹ́-ọwọ́, àti ti ìmọ̀-ẹ̀rọ fún àwọn ènìyàn lápapọ̀. Àǹfààní tó dọ́gba ní ilé-ẹ̀kọ́ gíga gbọ́dọ̀ wà ní àrọ́wọ́tó gbogbo ẹni tó ...
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
Maálù aláwọ̀ dúdú àti funfun
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
Ejò lórí ẹ̀ka igi
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
Kòkòrò oyín mẹ́ta àti òdòdó mẹ́ta
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
Òkójọpọ̀ àwọn ìwé akẹ́kọ̀ọ́
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
Kéèkéé afẹ́sẹ́wá
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
Ìwé mẹ́fà lórí ara wọn
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
Oṣùpá tó tàn lórí omi
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
Ewéko níwájú ìfèrèsé
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
Bọ́ọ̀lù níwájú ajá dúdú
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
Oòrùn tó tàn l'ẹ́hìn sánmà
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
Ẹṣin tó wà níwájú oòrùn
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
Èso ápùù òdidi kan àti àbọ̀
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
Àwọn òkè
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
Ìdamẹ́wàá mílíọ̀nù kan ní ẹgbẹ̀rún lọ́nà ogọ́rùn-ún
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
Maálù ń jẹ koríko l'ẹ́gbẹ̀ẹ́ igi ńlá, Oòrùn sì ràn l'ókè wọn
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
Odò adágún láàárín àwọn òkè
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
Ẹgbẹ́ àwọn nóòsì kan
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
Ọmọkùnrin láàárín bàbá àti ìyá rẹ̀
WAXAL_YOR_F1
unknown
waxalnlp
female
End of preview. Expand in Data Studio

No dataset card yet

Downloads last month
842

Models trained or fine-tuned on voicedata/final_yoruba