Dataset Viewer
Auto-converted to Parquet Duplicate
text
stringlengths
12
391
English Sentence
stringlengths
5
1.03k
Ajínigbé ti pa èèyàn mẹ́wàá láàrìn oṣù mẹ́ta.
Ten people have been killed in three months of fasting.
Tí o bá lọ sí ilẹ̀ òkèrè fún ìgbà àkọ́kọ́, àwọn ènìyàn lè ṣe sùúrù pẹ̀lú ẹ, nítorí wọn mọ̀ pé àwọn arìnrìnàjò ní orílẹ̀ èdè tuntun nílò láti farasinl.
When you go to a foreign country for the first time, people can be patient with you, knowing that people new in sign language are needed.
Ọ̀ṣunfúnkẹ́ kìí se ọmọ ẹgbẹ́ wa, alárinà lásán ni ó jẹ́.
Osunfucker is not a member of our party; it is only a person who is a habitual “night” wanderer.
Mo nífẹ màmá mi.
I love my mother.
Àmọ́ṣá, síse àwárí ibojì rẹ̀ ní 1922 sọ ọ́ di olóòkìkí. Niigbàtí wọ́n ja ọ̀pọ̀lọpọ̀ ibojì látẹ̀yìnwá lólè, ibojì yìí nìkan ní wọ́n fi sílẹ̀ láì fọwọ́kàn.
But finding its bets in 1922 led to a luxurious end. It was completely and securely removed from the group stage.
Mẹ́sì fi àbàrá kékeré gba ńlá lọ́wọ́ ẹgbẹ́ rẹ̀.
The tender youth has received a special guest from his group.
Ni gbogbo 1960S Bresinski sise fun Johannu F Kenedi gege bi onimoran re, o tun sise fun isakoso Lindoni B Jonsin.
All over the 60S Fresinski beat Johannu F Kenyan Eagle, and in a statement, he beat Senator B Jonsin.
Túndé ń ṣaáyan láti gba ẹ̀mí àwọn mọ̀lẹ́bí ẹ̀ là
He is again grieving to save the life of his family
Ìyókù rẹ̀ má dàbí òjò ní island, ṣùgbọ́n kòsí omiyalé tí a ti gbọ́.
The rest of the island is not as much as the rain, but no flooding has been reported.
Ìyàwó mẹ́fà ni wọ́n fẹ́ nígbà tí wọ́n wà ní ìlú ìdànrè.
While in the city of lepers, they married six wives.
Àwọn ẹlẹ́gbé oníìjàkadì náà gbóríyìn fún Luna.
The insatiable person praised Luna for her positive attitude.
Nígbà tí mo lọ sí ìlú ọba, mo pàdé àwọn ọmọbìnrin méjì.
When I left the king's city, I met two girls.
Àmọ̀tẹ́kùn kò lè so èso rere nílẹ.
A thing in which one reposes one's trust does not make a good result.
Ìjọba ti ń gbẹ̀rọ ìgbàlódé láti pèsè fún àwọn eléré orí ìtàgé
The government is planning to provide electronic media outlets
Kúnlé àti Afọláyan gbéná wojú ara wọn lórí ayélujára.
He-who-has-happened-the-last-of-all-things-disappear.
Àwọn olè ja ilé ìfowópamọ́ náà.
FULL LIST OF SUPER EAGLES THAT HAS ARRIVED.
[snap] Ẹ má lọ sínú igbó lóru o.
[snops] Don't get into the bush overnight.
Síwáájú si lẹ́yìn ìsọ̀tẹ̀ náà àyè láti sisé si´ sílè fún gbogbo àwọn òlùbèwò okùnrin èyí tó fi àyè gba àwọn to ní ìtalára àti pẹgẹdẹ́ jùlọ láti sẹ àsèyor.
Immediately after the attack, representatives from the Finland branch office, the local circuit overseer, and local elders provided comfort and support to those affected by the tragedy.
Àwọn òṣìṣẹ́ padà sí ẹnu iṣẹ́ ní ìpińlẹ̀ Ọ̀ṣun.
Officials have returned to the office in Oṣun State.
Ọlọ́pàá fẹ́ k'áwọn oríadé parí aáwọ̀ láàrín Ìgbòho àti Ṣèyí.
The police demanded that the hearings be completed between Igboho and Seyi.
Aláàfin Ọ̀yọ́ yóò wọ káà ilẹ̀ ṣùn ní ààfin lọ́sẹ̀ tó ń bọ̀.
The Ọ̀yọ́ lawmaker will issue a 6:00 p.m. curfew.
Àwọn onímọ̀ ìjìnlẹ̀ sáyẹ̀nsì láti ilé ìkẹ́ẹ̀kọ́ gíga ti ìsègun Stanford lọ́jọ́ ajé ti kéde ìdásílẹ̀ irinṣẹ́ ìwádìí tuntun tí ó le tó nǹkan lẹ́sẹẹsẹ pẹ̀lú bí wọ́n bá se rí: irinṣẹ́ kéreké tí a lè tẹ̀ jáde pẹ̀lú lílo irinṣẹ́ ìtẹ̀wé ìgbàlódé pẹ̀lú owó ẹyọ fún ọ̀kọ̀ọ̀kan.
Technical and backroom experts from the University of Stanford, Dr. Rutherford, France, France, France, France, France, France, France, France, France, France, France, France, Spain, Spain, Spain, Spain, Spain, Spain, Spain, Spain, Spain, Spain, Serbia, Serbia, Serbia, Serbia, Serbia, Serbia, Serbia, Serbia, Serbia, Serbia, Serbia, Serbia, Serbia, Serbia, Serbia, Serbia, Serbia and Serbia.
Ìgbà márùn-ún rèé tí ajìjàgbara bọ́ lọ́wọ́ ìkọlù láti mu.
Five times the person with smooth cheeks came to the aid of an insatiable person to drink.
A mọ ìlú Argentina nitorí wọ́n ní ẹgbẹ́ polo àti òṣèrè ní àgbáyé.
The Bible Teach book in Macedonian that the goatherd received ten years earlier During the campaign, one of our brothers met a goatherd on the road.
Egbére jẹ́ ẹ̀yà iwin kan.
Unrestrained dancing is a great insult.
Èyí ló gbajúmọ̀ jù láàrin àwọn tó ti fi iléẹ̀kọ́ sílẹ̀, èyí tó fún wọn láàyè àti gba ààyè ọdún kan sáájú iléẹ̀kọ́ gíga fásitì,láláì gbégirénà ètò ẹ̀kọ́ wọn.
This is most widely reported among school closures, where they were able to meet for a year before high school closures without any gaping down on their education systems.
Àwọn aṣòfín ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ti yọ Abẹnugan Ilé bí jìgá.
The soap seller in Oyọ State has let Benugan go as a sacrifice to one's house.
Ọọ̀ni ṣàlàyé ìdí tí àwọn ọba Èkìtì fi yàtọ̀ sí àwọn ọba kan.
It is one of the reasons why some of the ruling kings are shiftless.
Awon etiosa yi je ti elebi ti ere maa n po si nigba miin, won ni orisirisi oja ni eti oda. Omi wiwe o lewu.
The bow-string is taut while it remains on the bow; the bow-string is taut while it remains on the bow.
Tí Allies bá kùnà, Ìlú Germany lè borí Britain bí ó ṣe borí àwọn tókù ní Europe.
If Allies failed, Germany will now be able to beat Britain by making a victory over the others in Europe.
Awọn ìsọ̀rí mìíràn ni, Àwòrán tó dára jù, Olùdarí, Àyàwòrán, Aṣaralóge, Asàtúntò-Fíìmù, Aṣàtúntò ohùn, Apohùnpọ̀, àti Akọ̀tà.
Some of the kits are the best pictures, Director, Video, Azuerologist, Azure-Femi, ASL, Apolog, and Aja.
Awon omode to ni ADD, o ma n soro fun won lati fokan si nkan bii ise ile iawe sugboon wo le fokan si awon nkan to ba wu won bii ere sise abi wiwo ere katooni ti won feran julo abi kiko gbolohun lai lo awon ami gbolohun.
The Africans were simply a different class from the (NPFL) champions, who though pulled two goals back late on to give them a fighting chance in the tunament.
Apia ni ipinle agbara Samoa. Ilu naa wa ni irekusu Upolu, o de ni eyan 40,000 o din die.
It is overgrown with broken gourd that Samao kills, and it is our pride that made landfall over Opulú, where we lived over 30,000 years ago.
[snap] Ìgbín jẹ́ ẹranko kan tí ó nífẹ láti máa sìn. [external]
[snap] The snail is an animal that is interested in serving. [external]
ọ̀kọ̀ láti ọrun oró wọn lè wọlé sí ìhámọ́ra ọ̀tá wọn. bíi 1000 B.C, ni àwọn Assyria gbé cavalry àkọ́kọ́ jáde.
experts from heaven can access their lessons through an enemy network. Assemblies are printed on the first official website, about 1,000 B.C.E.
Àwọn agbébọn ń jí ọmọdé gbé nílùú Èkìtì.
Firefighters raid a child carrying fourteen hundred juju gourdlets in Èkíte.
[breath] Wọ́n kì ń fọnu fún ọmo ̣ìkókó.
[browns] He-who-would-not-collect-rain-water usage.
[breath] Onígèlè yaya ni màmá yẹn.
[browns] The mother's assailants came to the aid of the masquerader.
Kí ló dé tí o sá aṣọ tútù sí inú ilé.
You had better run from the washing machine.
Ilẹ̀kùn yàrá Tádé ti bàjẹ́.
The leopard's stealthy gait has been destroyed.
Àwọn agbébọn kọlù àgọ́ ọlọ́pàá márùn-ún lásìkò ìwọ́de.
Firefighters have raided five officers for the first time.
[breath] Agbẹjọ́rò ní kí o wá sínú yàrá ìgbẹ́jọ́ láti wá jẹun.
[browns] Please come in to the court sessions to eat food.
Bi o se n pada lo ile leyin to ti gbe oke okun, o ti yiwa pada si asa titun o de ti padanu awon isesi re to wa lati asa ile re.
While on a visit to the prison library, the guard asked me, ‘What did they tell you on the phone?’
Wọ́n ní àwọn ọmọdé wà nínú àwọn tó sá fún ẹ̀mí wọn.
There are children among those who are saved from execution.
Adé bẹ̀rẹ̀ sí ṣa agbébọn jáde nínú igbó Yorùbá.
When the incident began, gunmen from Yorùbá Forest attacked the village.
Iyá ọba náà tún wà níbẹ̀.
Also there is the king's mother.
Ara ò ní ni wá o.
He will never again go searching for a body.
Nítorí Ayọ̀délé ni Ààrẹ orílẹ-èdè márùn-ùn fi bá ara wọn jà
Five nations are fighting one by reason of the problem posed by the founding fathers.
Bí o bá ń bọ̀ wá sí ibùdó, mú àketè tàbí ibùsùn láti mú ọ jìnà sí àwọn ejò, àkekèé àti àwọn irú wọn ni.
As you get to the station, get a kite or a bed made from a snake, beads, and people like them.
[snap] Àwọn olópò náà gbìyànjú púpọ̀.
[snap] The players made a lot of efforts.
Àwọn mẹ́fà tí a gbé pamọ́ pẹ̀lú àwọn ọmọdé àti àgbàlagbà ni wọ́n ti fi sílẹ̀ àti àwọn Filipino tó jẹ́ ayàwòrán.
Six children and adults tied in at the full-time whistle have been released from the group stage.
Àìsàn Márùndínláàdọ́rùn ni wọ́n wòsàn.
The treatment was followed by a 15-year-old.
Ìjiyàn náà bẹ̀rẹ̀ láti àríyàn jiyàn lóri owó ìtura àtí àtúnkọ́ ilé ní ìgbà Ọrikénì, tí àwọn konsafetifu tí fi yẹ̀yẹ́ sọ lórúkọ “Ìṣòwò Olinsi Titun Buṣì”.
The controversy spawned controversy in the controversy surrounding the controversy surrounding the controversy surrounding the controversy surrounding the controversy surrounding the controversy surrounding the controversy surrounding the controversy surrounding the controversy surrounding the controversy surrounding the football competition.
A fẹ́ lọ dá aṣọ náà padà sí ilé aránṣọ.
We really wanted to get the cloth back into the house.
[snap] Ilà gọ̀m̀bọ̀ ni Tìmílẹ́yìn kọ.
[snap] Timiliary language.
Àwọn tó ṣèsẹ̀ gba yàrá tuntun lókè ní afínjúgidi ni.
All in the facility were in a procession with players carrying a new room.
Èyí ni àwọn ìgbà mẹ́jọ tí ọ̀rọ̀ Olúwo di ariwo.
As a result, eight times were heard regarding the Owner-of-the-universe’s language.
Ìriìn àjò nínú ọkọ̀ òfuruufú lẹ jẹ ìrírí ìjayà fún èyàn lóórẹkóórẹ, pàápàá júlọ tó bá jẹ pé wọn kò tìí fò télè tàbí wọn ti ní ìrírí tó banilérù.
Heavy rainfall from the storm caused severe flooding, especially when it proved that they had no flight or were facing a tornado.
Odòlayé Àrẹ̀mú jẹ́ olórin kan tó gbajumọ̀ ní ìlú Ìlọrin
A song that rumbles at Ilorin
A ti kéde kónílé-ó-gbélé ọ̀sẹ̀ kan lásìkò tí ìdìbò yóò wáyé.
We have announced a one-week-long building down at the time of the disaster.
Ìkan lára àpẹrẹ́ má le gbàgbé ti ìkéde North Atlantic ti WWII. Àwọn Amẹ́ríkà ń gbìyànjú láti gbé àwọn ọkùnrin àti àwọn ǹkan èlò kọjá Atlantic Ocean láti ran Britain lọ́wọ́.
One example of this is the case with the announcement of North Atlanta, WW000. The United States is making a concerted effort to accommodate men and women through the Atlanta Ocean in their efforts to assist Britain.
Àwọn onígbàgbọ́ máa ń wa ìríri tààrà́, ìmọ̀́lára tàbí fi ojú inú wo ohun tótọ́ ti ọ̀run tàbí àwọn alálẹ̀ òrìsà.
It is only those in the faith that take a closer look at the things of heaven or the gods.
Wọ́n ti mú Èmánúẹ̀lì lọ sí ibi tí yóò ti kọ́ bí wọ́n ti ń ṣe bàtà.
Imamele was transferred to the station to learn how to practice shoes.
Ìdájọ́ òdodo nìkan ni mò ń bèèrè fún lórí ọ̀rọ̀ Bàbá Ìjẹ̀ṣà.
I ask only a fair verdict on the patriarch's case.
A ti rí ṣálángá tó ṣẹkù nínú àwọn ilé ní agbègbè Minoan ti Crete àti Santorini ní Greece.
It has been reported that some of the homes in the towns of Minoan have been destroyed in the lands of Crete and Santini, Greece.
Ìwádìí fihàn pé ìdajì àwọn gbájúẹ̀ lágbàyéé wá láti Nàíjíríà
Studies have shown that only half of the victims have come from Nigeria
Àmọ́ ààrùn olóde ò jẹ́ kí àwọn òṣìṣẹ́ ṣisé owó tí wọ́n gbà.
However, a regular payment is not to be prescribed for the workers concerned.
Àwọn olùpèsè VPN (ìtàkùn aláfojúrí ọlọ́danni) jẹ́ ọ̀nà kan tó dára jùlọ láti wá ọ̀nà àbáyọ sáwọn ọ̀rọ̀ òṣèlú tí a fi pamọ́ àti dídí ìdúrógbaari okoòwò.
The National Bank’s (NPN) administrators are one of the best ways to find out what the protections do and how to stop the fight against corruption.
[snap] Ìrìn àjò láti Èkó sí Ìbàdàn tó wákàtí méjì ààbọ̀.
[snap] A trip from Lagos to Ibadan took us two hours.
Oorun ko ni erun ti a le duro le lori bi Aye se ni. Gbogbo ara orun ni a se pelu gaasi, ina ati pilasima.
The bow-string is taut while it remains on the bow; all-eggs remain on the bow-string, but all-insults remain on the bow-string.
Gbogbo àwọn èèyàn ló kópá láwùjọ tí wọ́n tún lo ìlànà ìrìnkèrindò. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn èèyàn ló ń sàríwísí ìlànà ìrìnlọrìnbọ̀.
All members of staff were also members of a community that also used social media handles, many of whom held observances via videoconference.
Middle order batsmen, Sachin Tendulkar and Rahul Dravid, ṣe dáadáa tí wọ́n sì ní ọgọ́rùn ún àjọsepọ̀.
Middle ordered a mission, Sachin Tendulkar and Ruhul Dravid, which was well-positioned and fifth-bound.
Orísìírísìí ìgbẹ́sẹ̀ ni ó máa ń jẹyọ nínú Ọdún Ifá.
It is a record number one kills in Ifá Year.
Eyín funfun ni arábìnrin yìí fi ń fa àwọn ọkùnrin mọ́ra
It is white yam that this sister is addressing the brothers
Ṣé ẹ ti gbọ́ nípa àrùn tuntun tó máa ń ba fóònù jẹ́?
have you heard about the latest HIV treatment?
Lára àwọn ohun tí a fi máa ń dáná nílé ni ìkòkò àti àdògán. [external]
Also among the substances we consume in the house are chickens and cane-fritters. [external]
Bi itan naa se wi, nkan to fi se iwuri nip e ko je gbajumo ni onakona. Awon ara Efesu, won ti binu, won kede pe ki won ma ko oruko Erostratusi lai lai.
If one's head was a pot and one gave it to a goat and developed a goitre. If one's head was not a pot, it did not eventually split open.
Èmi náà lọ mu bíà díẹ̀ níbẹ̀ ni nírọ̀lẹ́ ọjọ́ yẹn.
I also went to a nearby village for a visit that day.
[snap] Ẹlẹ́pà ìjẹ̀bú — èyí tí o fẹ́rà gaan — wà ní ìtòsí.
[snap] The Police Force—where you are going to be—is on the move.
Púpọ̀ àwọn obìnrin yí gan a máa lówó ju àwọn ọkọ wọn lọ.
It is much more women that will come to terms with men than with men.
Ìjọba kò fẹ́ ìpẹ́jọpọ̀ mọ́ nítorí kọ̀rọ́nà.
The government does not like to meet together due to the lack of communication.
Odo Onega naa ha mo Folga, tori na o seese ki o fi Rosia wa lati Okun Kaspiani.
Owo-Oleg, I am very grateful for the privilege given to Russia by our dear Akun Caspiani.
Ó seése kí oùnje òwúrọ̀ kọ pẹ̀lú àwọn ìpèsè aládìídù ẹkùn náà tàbí àsè pàtàkì tí agbàlejò.
While on a visit to the prison to the prison library, the guard asked the guard, “Why don’t you be afraid and report this to the police?”
Kẹ́rẹ́sìmẹsì jẹ́ ọ̀kan lára ìsinmi tó se pàtàkì jùlọ nínú ẹ̀sìn Krìstẹ́nì, ó sì tún jẹ́ àjọyọ ọjọ́ ìbí Jẹ́sù.
Christmas was one of the most important spiritual milestones in the history of Jesus Christ.
Mo sọ fún Ajírébi pé tí ó bá ti ráyè kí ó wá kí mi nílé.
I told him that if he is ready to visit me, I should visit him.
Ibi tí àwọn nọ́ọ̀sí ti ń ṣiṣẹ́ kò pójú òṣùwọ̀n rárá.
The use of blood transfusions, in part, was not worth the cost.
Láti padà sí ipò agbára titélè, wọn gbọdọ̀ mú ìfikún agbára èyí tí wọn gba láti ara ìmólẹ̀ kúrò.
To return to the top of the world power, they must lift this lift from the brain.
Kíni àwọn nǹkan tí kò hàn nípa arákùnrin tí ọlọ̀pàá tì mọ́lé?
What information is missing about the brother about whom the police have been visiting?
Ta ló gbé ọmọ jù sórí àkìtàn?
Who has put a child on the hilt of the story?
[breath] Ní àná, ò ń wò bí ẹyẹ t’ójò pa.
[browns] At night, you might look like a dog on a journey.
Àwọn èèyàn kan ní mo fẹ́ lù wọ́n ní jìbìtì
Some people said I wanted to kill them
Awon ojo to gun ju ni igba ooru le muu ki o soro lati ri orun to peye sun ati awon ailera bee.
The bow-string is taut while it remains on the bow; the bow-string is taut while it remains on the bow.
Ìkọ̀ọ̀kan ẹ́písòòdù yìí yó ò fojúsun àkórí nínú ìwé kan pàtó, tí a ó sì má a sàmúnlò àwọn àkórí yìí nípa lílo ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìtàn.
This one photocopy of the museum will not be pulled to the top of a certain book, and we will not use these principles across several narratives.
Wọ́n ti múná lọ.
He has been taken away.
Sóyínká sọ pé Nàíjíríà ti dojúrú, òun kàn ń wòó níran ni
Seyńka says Nigeria is in fashion, and she's been seeing it in the morning
Adé gbàlejò akọ̀wé Amẹ́ríkà lánàá.
The deaf person invited an American scribe to an open house.
Ajálékokò tún ti fi ọkọ rẹ̀ kọju irin.
She has also given in to her husband for the gadfly.
Ẹdun náà ni wọ́n pè ní ọ̀bọ.
The same is true of the vulture.
Ẹgbé òṣèlú wa kò se ìpàdé pẹ̀lú ẹgbẹ kankan o.
Our political group has formed a non-partisan group meeting.
Ìyàwó yìí máa ń gbá ọkọ rẹ̀ létí lẹ́ẹ̀kọ̀kan.
This wife remembers her husband on a one-sided note.
End of preview. Expand in Data Studio
README.md exists but content is empty.
Downloads last month
14