text
stringlengths
12
391
English Sentence
stringlengths
5
1.03k
Àwọn jàndùkú jí ọba kan gbé, wọ́n sì gbée sálọ sínú igbó
The mob assaulted a king and had him thrown into a bush
Ìjọba sọ pé kí wọ́n ka gbogbo ẹranko igbó àti ẹja inú omi
The government ordered the arrest of all wild animals and fish in the river
Wọ́n ti da ìdọ̀tí sọ́nà lẹ́ẹ̀kansíi.
Disgrace has been once and for all time.
Ìjì òtútù pa èèyàn mẹ́sàn-án ní Amẹ́ríkà.
In the United States, nine people were killed in the latest boat cap.
[breath] Kẹ́ẹ tún ilé ṣe kí a tó dé.
[browns] Do the house thing over and over again before we get to the station.
Ọ̀pọ̀ ọmọ orilẹ̀ èdè yìí ló ń jìyà nítorí ìwà ìbàjẹ́ wọn.
Many Nigerians suffer from the tragedy because of their own corruption.
[snap] Ilẹ̀ ti mọ́ bá àwọn ọ̀daràn yẹn. [external]
[snap] The country has committed crimes. [external]
Ọgbọ́n ló gbà tó bá ti jẹ́ ọ̀rọ̀ obìnrin.
He only paid attention to women’s talk.
Máṣe bá ojú òpó náà jẹ́ nípa ṣíṣà mí si tàbí àwòrán tó wà ní ogiri.
Disgrace comes upon me or a picture that is also in the bush.
Àsìkò àjàkálẹ̀ ààrùn yìí jẹ́ kí n di télọ̀ tó mọṣẹ́ gidi.
During this ordeal, I was able to become very well-positioned.
Oun tí mo gbọ fihàn pé àwọn kan ń dọdẹ mi nínú ìlú.
The one I saw was actually starving in the city.
[snap] Tó bá di ọdún tó ń bọ̀, mo fẹ́ lọ ṣe ọdún Kérésì ní ìlú mi.
[snap] And next year, I wanted to go celebrate Christmas in my city.
Nínú ọkọ̀ akérò aláràọ̀tọ̀, gbogbo ènìyàn nì ó lọ́pọ̀ àti ìgbárùkùtì, ìlànà ìrìnlọrìnbọ̀ tó dá l´rí àwọn ọkọ̀ aláàdáni.
In high-speed hoes, there are a lot and we don’t have goalkeeper problems, we don’t have goalkeeper problems. We don’t have goalkeeper problems – we don’t have goalkeepers – we don’t have goalkeepers in the country – we don’t have goalkeepers – we don’t have goalkeepers in the country – we don’t have goalkeepers right ...
O ní àgbẹkalẹ̀ mólíkuúlà kan náà yálà o jẹ aféfé gaasi, olómi, tàbí ní lìlẹ.
You have one hundred cowries in savings whether you eat yams, yams, or yams.
Ilé ẹjọ́ dá Babátúndé padà sí áhàmọ́ọ́ látàrí ẹ̀sùn gìbìtì.
The court sentenced Babatunde to prison for his evading arrest.
Òṣùwọ̀n mẹ́jọmẹ́jọ lóri omi.
eight months of probation.
Ṣèyí Mákindé ní ààrùn jẹjẹrẹ kò leè borí òun.
Mákinde says he cannot heal.
Nígbàtí gbogbo àwọn ohun àmúlò bá jẹ́ lílò káàkiri àwọn ẹ̀ka tó ń ṣiṣẹ́ ní àjọ, ìṣẹ̀dá àti níní ọpọlọ lè wáyé.
Every facility can be used across branches that work within the organization, creation, and brain.
Ọmọ bíbí ìlú Ìbàdàn ni Ààrẹ wa.
The President is the birth of a child in Ibadan.
Ọmọ màmá ẹ ni Túndé.
Núnde is your mother's child.
Àrẹ̀mú àtàwọn àgbà Yorùbá míì sọ ọ̀rọ̀ sí wa.
My contacts and other elders in Yorùbá speak to us.
[snap] Ẹsẹ̀ ẹran náà ti kán.
[snops] The bone of the meat is sharp.
Àwọn àgbàgbà ọlọ́pàá ti ṣàánú ọmọbìnrin tí wọn gbámú
The police authorities have pity on the injured girls
Agbapo ere sisa ni irinajo agbaye, Go Running Tours, se netiwooki fun opo awon olupese wiwo era sisa ni continent merin.
The followed is the home of the Nigeria Football Federation boss, Gorønging Tourist, who made the assertion in a statement issued on Wednesday.
Ọkọ̀ ojú òfúrufú Turkey ma ń fò lọ sí ibùdó mọ́kàndínlọ́gbọ̀n àwọn orílẹ̀èdè ilẹ̀ adúláwọ̀ ọgbọ̀n ní bí i ọdún 2014.
Turkey is now tipping forward on 90 international airport terminals in the Bicol region of southern Luzon, the largest island of the Philippines, as a result of the 2014 earthquake.
Mo ti jẹun ní òwúrọ̀ yí.
I have always eaten in the morning.
Ọba Augustus gbàwọn onímọ̀ ìsègùn òyìnbó, bakanáà lótún sàgbékalẹ̀ ikọ̀ onísègùn ilẹ̀ Róòmùn àkọ́kọ́ láti lò lẹ́yìn ogun.
The August king refuelling power out of the army until the government’s first refuelling power out of the country at the rear of the column.
Tọ́lá tún wá sí ààfin láìmú ọkọ wá.
Olatila also came to the court sessions when her husband came without a husband.
Ọ̀gá báńkì rí ẹ̀wọ̀n ọdún mẹ́jọ e lórí jìbìtì owó oníbàárà.
The Chief Bank found eight years old sentenced to four years in prison for so-called white mangroves.
Làásìgbò bẹ́ sílẹ̀ nílùú Ẹ̀kọ́ lánàá.
The muslim says “let’s roll”.
Ẹ̀mí ọlọ́pàá méjì bọ́ nílùú Ẹ̀kọ́ lánàá.
Two wind-forced police came to Lagos yesterday.
Fọláshadé Tinúbú ti di Ìyálóde ìlú Iréwọlédé àti Owódé
Insults are now available in Ayaloye, Irewolande, and Owodẹ
Ẹbí ìjọba ni kò gba ìdáǹdè akẹ́kọ̀ọ́bìnrin náà.
The young publisher’s education is not taken for granted by a government family.
Pẹ̀lú pé ó dàbí pé wọn ò mọ̀ọ́ṣé lẹ́gbẹ́ àwọn ẹgbẹ́ wọn lápá guusu, Ilu Afrika alapa guusu túbọ̀ n ṣe dada bí ídíje náà ṣe n lọ.
Despite the fact that I might not have been from their group group group stage, I went through a thorough process and I started to get a sense of Jehovah’s name.
Àwọn agbébọn pa ìyàw olóṣèlú kan ní Ìbàdàn.
Shooters killed a political woman in Ibadan.
Mo mọ bí mo ṣe ń ṣiṣẹ́ tí mo fi ń rówó.
I know how I work while I make money.
Ìjọba gbé òṣùbà fún àtìlẹyìn aráàlú lásìkò yìí
The government has put forward the month-long plan to get rid of the country
Ọmọ Àjàó ké pé àwọn gbájúẹ̀ fẹ́ forúkọ bàbá rẹ̀ gbowó ìsìnkú.
The son of Ọ̀jàò is called upon to register for his father's death.
Ní 1976, ìda ọgbọ̀n ti Machu Picchu tí ní ìdápadà ó sì tẹ̀síwájú títí di òní.
And in 1975, an additional half-time Major champion, Machu Pinchú, passed on.
Àrẹ̀mú ti relé ẹjọ́ nitorí ẹ̀sùn tí wọ́n fi kàn-án
The verdict is in the process of being convicted
Tí o bá rí ara rẹ pé ò ń yí ọwọ́ ago padà ní ojú àlá rẹ, o le è gbé sí òdi kejì yàrá ní ibi tí ọwọ́ rẹ̀ kò tí ni to o láti pa á.
If you see yourself tinging your palm-wine producing palm-tree in your own eyes, you can still go to a second house at a designated time.
Ìyàwó kékeré tí arákùnrin ọ̀hún fẹ́ ló ba gbogbo nǹkan jẹ́.
The little wife that the brother wanted to kill got destroyed.
Ọmọ tí a bí tí ó ń súnkún tọ̀san tòru.
A child we give birth to and we give only one bundle of thatching grass.
Ó pọn dandan láti rán wa létí pé Káàárọ̀ Oò Jíire ni wá. [external]
It is time to get out of here, and we need to remember that we came tomorrow morning. [external]
Ẹgbẹ́ aṣòfin ilẹ̀ yìí ní ìjọba ń tẹ ẹ̀tọ́ olùdíje ààrẹ́ tẹ́lẹ́ náà lóju
The Senate also urged the agency to always acknowledge only accredited personnel to be allowed in restricted areas of the airport.
Àbájádẹ àyèwò fihàn pé Arias ti kó aàrùn náà ní íwọn bíntín, Òjísé Ààrẹ Rodrigo Arias fi síta.
The result of the anesthesiologists’ assessments was presented on 60 minutes of probation.
Kò bìkítà bóyá ó dára tàbí kò dára.
She is not sure whether it's good or not.
O ṣeéṣe fún àwọn onímọ̀ sáyẹnsì latí pinu pé ohun dúdú ma ń ran ohun dúdú mín bí ohun désé ṣe ma n ràn án.
You can also scientists believe that what I'm doing is what I'm doing that I'm sorry for not doing what I'm sorry for.
Mo gbé ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìgbésẹ̀ láti lóyún kí n tó rí ọmọ́ bí.
I have taken a lot of steps to pregnancy before I could have a child.
Níbí ọjọ́ se ń gorí ọjọ́, ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọ̀rọ̀ tí wọ́n yá láti Germany dirapọ̀ di ọ̀kan. Èyí ni ìbẹ̀rẹ̀ ìlàlọ́yẹ̀.
As the day sets, the number of those who came from Germany rose to a level common. And that is the beginning of the problem.
Ẹniafẹ́ ti parí ilé ìwé gíga.
The lazy person has completed his university education.
Sibe si, ti o ba ko lati se, o leyin: idiwo idagbasoke, ailounje, ati iku bopeboya.
Sitting, and you will find no helpers, and you will find no helpers: beads, yams, and bean fritters.
Jas 39C lọ kọlu ibi tí ènìyàn ma ń gbà ní ago mẹsán àbọ̀ (0230 UTC) ó sì jọ́nà, tó sì ti àwọn ọkọ̀ òfuruf;u pa.
The Damaturu- based boys sustained the pressure until the 79th minute, when their car was suddenly swept away.
Àwọn ẹgbẹ́ kan ní kí ìjọba dá wọn lohùn lórí owó oṣù.
Several groups requested that the government also sign a 6:00 p.m. curfew.
Ìrẹsì àti ẹ̀wà ni oúnjẹ tí mo fẹ́ràn jù.
The food I liked most was tennis and tennis.
Ètò ìsìnkú olóògbé náà yóò wáyé láì pé.
The last spouse of an elephant will find out.
Ọ̀rọ̀ òṣèlú kọ́ ló gbé mi lọ sọ́dọ̀ Bọ́lá, àbẹ̀wó lásán ni.
I was not taken to Bola, I was only a paid doctor.
Perry ṣe àlàyé wípé òhun o ‘padà sí Texas láti ṣe ayèwò àbájáde ifikùnlukùn ẹgbẹ́ lálé òní, pinnu bóyá ìtẹ̀síwájù wà fún mi nínú ìdíje yìí.” Ṣùgbọ́n lẹ́yìn náà o sọ wípé òhun o tesíwájú nínú ìdíje láti figagbága nínú idibò abẹ́lẹ́ ọjọ́ kọkànlélógún oṣù kìíní tí gúúsù Carolina.
Perry explained that he was ‘overwhelmed in Texas to conduct a full-time analysis of the group’ today, determining whether I was involved with this competition.” But afterward he announced that he wanted to continue his campaign on the 21st minute of South Carolina.
Wọ́n lè ṣeré eré ìdárayá ìjà ẹlẹ́ni mẹ́ta ìgbàlódé ní ìpele méta, láti akẹ́kọ̀ọ́ tó wà ní ilé ẹ̀kọ́ àgbà sí àkọ́ṣkmọṣẹ́ àti ìdíje Olympics.
They can compete with three players in three goals, from university days to Olympic Games.
Màmá mi, mo ti yó.
Thank you to my mother, I have.
Gómìnà ti fi owó ránṣẹ́ sí àwọn aláìsàn tó wà nílé ìtọ́jú
The Governor has donated money to patients in hospitals
Ó tún le se àǹfànní fún ènìyàn láti ra Wild Card, èyí tí yíó pèsè ìwọlé sí bóyá àwọn ibùdó ní ilẹ̀ South Africa tàbí àwọn ibùdó àpapọ̀ tàwọn ènìyàn South Africa.
It also provides opportunities for people to sell Wild Card, which will allow them to receive access to other parts of South Africa or the same number of South Africa.
Wọ́n dá ìlú Apia sílẹ̀ ní àwọn ọdún 1850, ó sì ti jẹ̀ olú ìlú Samoa láti ọdún 1959.
The city of Apia was evacuated in 1850 and has been in the capital of Samao since.
Wọ́n fẹ́ fi àwọn àgùnbánirọ̀ rọ́pò àwọn olùkọ́ ni àdúgbò yẹn.
They wanted to replace teachers from youth-based group mates with teachers.
Ọpọlọ ọmọ yẹn dà bíi ti Dámilọ́lá.
The child's brain is like the divining string.
Yọ̀mí ní àwọn ti parí ìlànà tó yẹ.
The oxygen says that they have violated the fundamental values.
Mo ti pàdé igba ènìyàn lópin ọ̀sẹ̀ ọdún tó kọjá ní Ilé iṣẹ́ Ọlọ́pàá
I have met a hundred people at the police station last weekend
Ó figbe s’ẹ́nu pariwo.
It stains a person's mouth and is in no pain.
[snap] Èní ni màmá Kọ́ládé yóò fi ilé ìwòsàn sílẹ̀.
[snap] Nursing mother of Kolada will leave the hospital.
Àwọn ẹranko kan bí i erin àti àgùfọn, má ń súnmọ́ àwọn ọkọ̀ pẹ́kípẹ́kí àti àwọn ohun èlò tóbágbà mun yíò fààyè sílẹ̀ fún wíwò tó dára.
Some animals, such as railways and tricycles, will not be able to access high-speed hotlines and heavy metals from there.
Ṣé òótọ́ ni pé Àkànni ti já gbogbo ojú òpó ìjọba Nàìjíríà gbà?
Has Èkòn been destroyed by the kindness of the Nigerian government?
Tọkọtaya tí wọ́n fọ́jú ń ṣẹ iṣẹ́ olùkọ́ bímọ mẹ́ta.
The shiftless couple are doing the first of three children.
Àwọn boulevard to fe, ile ti o ni jigi ni iwaju ati oja igbalode ni a fi aja oni taili pupa seso won, oja senturi kejìdílógún, ati awon mọ́ṣáláṣí ati ṣọ́ọ̀si, biotilejepe ilu naa ni afefe to ile Yuropi Mediteraniani ju ile Turkeyi ibile lo.
Ebonies to the velvet, says the pair are two hundred and forty-four hundred buffaloes with eight hundred horns, and forty-four hundred buffaloes with eight hundred horns, and forty-four hundred buffaloes with eight hundred horns, and forty-four hundred buffaloes with eight hundred horns and forty-four Europeans with ei...
[snap] Aṣọ ìbora wọn dà ná; níbo ni wọ́n fi sí?
[snap] Their newfound yams are torn open; where did they get them?
Àmàlà ni Simi jẹ fún oúnjẹ ọ̀sán.
Simi is a lazy person who must have a weekend to go to roost in food.
Jẹ́ kí á lọ bẹ̀rẹ̀ ìgbé ayé tuntun níbi tí enìkan ò ti mọ̀ wá.
Let's get down from a new life where we don't know anyone.
Virginia ni wọ́n ti ṣe ẹjọ́ náà, nítorí ibẹ̀ ni ilé àwọn ile iṣẹ tó ń pèsè intanẹtì tí ó ga jùlọ tí a mọ̀ sí AOL wà, ilé iṣẹ́ tí ó bẹ̀rẹ̀ ìgbówólélórí.
Virginia was convicted of so-called ‘harmless’ service that the company contracted to industrial layouts.
O ṣé tí o rán mi létí.
You did what you told me.
[snap] Láti ìlú Àjàṣẹ́ ni màmá ti wá.
[snap] Nursing mother's from Lagos.
Ọ̀pọ̀ ọ̀gá òṣèré ló ń bèèrè ìbálòpọ̀ lọ́wọ́ àwọn ègbè lẹ́yìn wọn
Many Nigerians in the diaspora have asked for their contact points
Orílẹ̀èdè Nàìjíríà lọ́wọ́ yìí kò lè fàyè ìnákúnàá sílẹ̀.
Nigeria is not allowed to roll back on progress.
Ẹ̀sùn àjẹbánu àti lílo owó báṣubàṣu la fi kàn olóyè náà.
The prosecution was held guilty of extortion and refusal to pay.
A ni isoro eto isuna ni nkan bi odun kan seyin, eyi ti o feju keke ni bi osu meji seyin, eyiti mo lero ni bayi wipe ojo isuna ti bere si ni gbera so pada bayi.”
It is the incessant chattering trick when one is satiated, but it is too much to handle; the cry “My hunting-bag is full!”
Owó epo tó yẹ kí ó ma díkù níṣe ló ń lékún si.
The cost of living palm-oil is the same as the cost of living.
Àwọn yìnyín tó ti là níwọn kó jọ, dí fi àwọn àsìá pààlà. Àwọn ohun ìkọlẹ̀ tí wọ́n ti se lọ́tọ̀ nìkan ló lè rìn ín, pẹ̀lú lílo ọkọ̀ fi wọ́ epo rọ̀bì àtàwọn ohun èlò.
FULL LIST OF SUPER EAGLES THAT HAS ARRIVED, LIST OF SUPER EAGLES THAT HAS ARRIVED, LIST OF SUPER EAGLES THAT HAS ARRIVED, LIST OF SUPER EAGLES THAT HAS ARRIVED.
Ẹni tó fí ìbínú lu Ábúdù ọlọ́kadà pa ní Abẹ́òkuta ti sálọ.
The person who antagonizes the Ẹbuù-He-who-has-an-affair-an-affair-with-one's-eggs-one's-affairs-for-losing-one's-one's-one's-one's-teeth in Abuja's-affairs-affairs-for-losing-one's-one's-one's-one's-one's-for-loss-one's-one's-one's-one's-one's-question.
Àwọn ìwọn iná tún kéré ju àwọn n´ kan tó kórajọ di àwọn ìwọn nkan tó gba àyè tó kéré jùlọ.
Firefighters are more than one can easily be produced as we have access to at least one place.
Èmi kọ́ lẹni tó n gbé àwọ̀ Fẹ́mi Adéṣínà wọ̀
I did not have a match with Femi Adesina
Ṣé nítorí Ànọ́bi ni Ọlọ̀run ṣe dáa yín?
Because of Onbọmi?
Gbogbo eyín Ìya Bọ̀dé ló ti yọ tán.
All hell has been let loose.
“CCTV ma fi àmì tó lágbára ṣọwọ́ sí àwọn ènìyàn tó ṣe iṣẹ́ pẹ̀lú àwọn ẹranko nítorí àláfíà wọn ló jù.”
“CCTV also delivers powerful points to people working with animals for the purpose of being OK.”
Iléeṣẹ́ nírètí àti wá ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọ̀nà tí èrè yóó fi má a wọlé tí wọ́ yóó sì fi di ìlú mọ̀ọ́ká láwọn agbègbè tí ìtàkùn Skype ti gbalẹ̀, bí i China, apá ìlà oòrùn Europu àti Brazil.
The ministry hoped to find many roads that were accessible and that were accessible in the areas covered by Skype, as in China, the eastern European Union, and Brazil.
Ṣiṣe ski lati oke giga delẹ, ti wa gẹgẹ bi ere idaraya lati bii sẹnturi 17th ati pe ni 1861, awọn ara Nọwe da ẹgbẹ ski idaraya akọkọ ni Ọstrelia.
The construction of the 17th-largest island in 181 has been underway in Austria.
[snap] Àrèó máa ń fi ìwà tútù tanijẹ.
[snap] A needle is used to make pounded yams.
Bíbíire, Tìmílẹ́yìn àti Ṣẹ́gun jẹ́ ọ̀rẹ́ tímọ́tímọ́.
The white man, the white man, the Ṣèngún person is a fit and proper person for any good.
Sopocies àti Aristophanes ṣì jẹ́ gbajúgbajà olùkọ̀wé eré àti pé àwọn eré wọn jẹ́ ìkan lára iṣẹ́ tó tóbi jù lọ ní lítírésọ̀.
Sopomies and Aristophenes are still the most widely cited book in history.
Mákindé ṣe ìfilọ́lẹ̀ ìgbìmọ̀ àlákòóso Àmọ̀tẹ́kùn.
Makinde inaugurated the Governing Body.
Ìkáyàsókè bá àwọn òṣìṣẹ́ nítorí àìmọ ohun tí yóò ṣẹlẹ̀.
Disgrace comes upon workers for lack of knowing what the future may bring.
Wọ́n mú ọmọ náà ṣeré.
The child was taken aback.
Wọ́n ṣe iṣẹ́ abẹ fun ọmọ yẹn ní inú.
The child was given a disease in which he was subjected to physical abuse.